cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ni ile-eko giga Birkbeck, Yunifasiti ilu London yi kanna an ni o ti gba oye Dokita lori OrganizOlùràpadà psychology ni odun 1987..
wikipedia
yo
Awon ise e re ti o ti se tele lo ni i se pelu ìfiwéra awon ipo ni aarin awon obinrin ile Geesi ati ti ile Naijiria..
wikipedia
yo
O gbéra lọ sí orílẹ̀-èdè Netherlands àti lẹhinna padà wá sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti o si tun ba rudurudu pupọ pade ni ọdun 2000..
wikipedia
yo
Lehinna, O gbéra lọ sí orílẹ̀-èdè South Africa níbití ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní Yunifásítì ìlú Cape Town..
wikipedia
yo
Ní Yunifásítì yí ni ó ti di olùdarí tí i African Gender Institute níbití ó ti ṣe ìrànlọ́wọ́ láti ṣe ìdásílẹ̀ ìwé ìròyìn ilé-ẹ̀kọ́ yí tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Feminist Africa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, Mama gba ipò kan ní ilé-ẹ̀kọ́ Mills ní Oakland, California, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ń lọ, ó ṣàlàyé nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ báyĩ í pé “Mo ti kọ́ pé Amẹ́ríkà kì í ṣe ńlá tàbí orísun ìjọba búburú”
wikipedia
yo
O parapọ̀ lati kọ́ kíláàsì tí wọ́n pè ní “Òfin tó dájú, Òṣèlú tó dájú” pẹ̀lú Arábìnrin Lee, ẹni tí í ṣe arábìnrin Ilé-ìgbìmọ̀ Ìjọba lórí àwọn àkọlé nípa àwọn obìnrin Áfíríkà àti Áfíríkà-Amẹrika, pẹ̀lú àwọn ipa lórí i àbọ̀, òṣì, HIV/AIDS àti ogún..
wikipedia
yo
Mama tún jẹ́ alága ti èè Èkó àwọn obìnrin ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ìlú California..
wikipedia
yo
Mama ni Alaga ti Igbimọ Awọn oludari fun Global Fund for Women, ati wipe o n gba oriṣiriṣi awon ajo agbaye omiran ni imọran..
wikipedia
yo
Ó ti fi ìgbà kan wà lára ìgbìmọ̀ àwọn olùdarí ti ilé-iṣẹ́ iwadi ìka ti Àjọ Àgbáyé fún Ìsókè àwùjọ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, ó ṣe àgbéjáde fíìmù náà tí í ṣe àwọn ajẹ́ ti GGga pẹ̀lú Yaba Be-ẹ̀rọ ó rẹ Mama ṣe àpèjúwe ara a rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi abo àti wípé òun kì í ṣe Wọmanist, tí ó sì jiyan wípé ọ̀rọ̀ nípa abo yí bẹ̀rẹ̀ ní ilẹ̀ Áfíríkà àti wípé àwọn abo tí ó jẹ́ funfun “kò í ti lágbára tó láti jẹ́ ọ̀tá dé bi wípé a ó ma fi ojú ọ̀tá wo àwọn ìjọba onírú àgbáyé àgbáyé..
wikipedia
yo
Ó ti tako ìjíròròrò lórí ìsókè àwọn obìnrin fún òguyìn àwọn ẹ̀kọ́ tí ó ní ìtunmọ̀ nípa ti abo..
wikipedia
yo
Ó tún ti jiyàn pé àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ilẹ̀ Áfíríkà ń tẹ̀síwájú láti fi hàn nípa àwọn òfin ti ìbálòpọ̀ láàrín ara ẹni àti àwọn ti abo..
wikipedia
yo
Apa ibi ti Mama ni ìfẹ́ sí jùlọ ni ti idanimọ akọ-abo bi o ṣe ni ibatan si ijagún kariaye..
wikipedia
yo
KRImọ́, 1989; Republished by WàtHiting and Birch, 1996..
wikipedia
yo
“Is it Ethical to study Africa? Preliminary thoughts on scholarship and Freedom"
wikipedia
yo
African Studies Review 50 (1), April 2007.Àwọn ìtọ́kasí àwọn òkọ̀wé ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Kehinde OlorunYomi ni wọ́n bí ní ọjọ́ ketala Oṣu Kini ọdun 1981..
wikipedia
yo
Ó ti kọ́ eré tí kòôkòô ti lé ní àádọ́ta tí wọ́n ti gbé jáde ní sinimá àti eré àtìgbà-dégbà ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ lórí èrò amódá-máwòrán..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ yi ti gbe ere marun un ti o laami-laaka jade, awon ni the Perfect Plan (2012), Forever within us (2014), One Moks in Time (2014), The Novelist (2015), Tẹsho (2016)..
wikipedia
yo
Eré The Novelist ni ó kalẹ̀ Kako ní Ile-Aran sinimá àti Ori Ero Oniga ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Cou's award Olorunsọ̀rètí gba ami-eye Ghana Movie Awards (ìpad) ni ọdun 2012 fun ere in the Cupboard ti Desmond Elliot gbe jade..
wikipedia
yo
Lára àwọn eré mìíràn tí Kehinde tun kọ ni Husband of Lagos Season 1 (2014) Fun ÌrókòTV, Missing Steps (2016) tí ó kọ nípa ìjọba orílẹ̀-èdè Switzerland àti Nigerian tí Charles Okafor gbé jáde òun ló tún kọ́ kó Oge's Sister ti Uche Jombo gbé jáde..
wikipedia
yo
òun ló kọ́ ojú ãnú tí ayọ̀ Adesanya gbé jáde, Bákan náà The Patient ti Ile-iṣẹ M-Net Africa gbé jáde.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí adarí eréeré couple's award ni ó sọ Kehinde di lààmì-laaka nídi iṣẹ́ dídarí eré, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé òun ló kọ́ èrè náà tí ó sì tún kkópa nínú rẹ̀.Ìgbé ayé rẹ̀Ọlọ́run ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Adéwùmí Odukoya ẹni tí ó jẹ́ amojú ẹ̀rọ̀ fún ilé ìwòran NexLáyével cinema ..
wikipedia
yo
Wọ́n bímọ ọkùnrin kan lẹ́yìn ìgbéyàwó wọn ní ọdún 2013.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1981Nigerian Actresses-Century Nigerian Actresses
wikipedia
yo
Abimbola FASholambola Fashola (ojo ibi 6 April 1965) o je obinrin akọkọ ni tele ati iyawo gomina ana fun ipinle Eko Babatunde Fashola.Abimbola FasholaorukoAbimbola EmManuela Fasholaojo ibi April 1965Ibadan, Ipinle Oyo, Nàìjíríàorile edeNaijiriaomo iluNaijiria Naijiriaise administrator Analitodaradun-Natashatẹ̀lé Fasholawebsiteofficial Websi Owayegbe aye ati ise bii ni 6 April 1965, ni Ibadan, olu ilu Oyo southwestern Naijiria.[2][3] O kẹkọọ Akowe ni The Lagoon Anatarial College ni Eko, nibiti o ti gba diploma Certificate..
wikipedia
yo
O tun pada gba iwe eri ni computer Science from the University of Lagos.[4] O sise die gegebi akekoo journalist at the daily Sketch ki o to darapò mo the services of the British Council ni 1987 sugbon o fise sile ni 2006 nigbati won fa ọkọ re Babatunde Fashola sile gegebi Flag Flag bearer of his Party and the governodicated candidate of the Defunct Action Congress of Nigeria.[5] AlÌyọnufoworola Buck-dejòkè Ore-lope-Adeji-ìtọ́kasí "My Love story with v Fashola-Lagos first lady"
wikipedia
yo
Retrieved 19 April 2015.Benin "Abimbola Fashola, symbol of humility"
wikipedia
yo
Retrieved 19 April 2015.Benin A, Jubril Ọlábọ̀dé (2012)..
wikipedia
yo
Nigerian Women of Distinction, Rosary and exemplary Presidential Qugan..
wikipedia
yo
ISBN9781466915541.CS1' "I don't Have an Eye for Politics But ...
wikipedia
yo
Retrieved 19 April 2015.Honorary titles byolumi Tinubufirst Lady of Lagos State-2015-ìyèeeded byláńlé AmbodeThis Nigerian biographical article is a Stub..
wikipedia
yo
Aeyasat Yusuf-Tunmire tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kẹfà Oṣù Kẹta Ọdún 1985 (6 March 1985) agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ọmọ Nàìjíríà nígbà kan rí..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Finland ni ó ń gbé báyìí.Yusuf ti gbá bọ́ọ̀lù fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ní Nàìjíríà àti Finland..
wikipedia
yo
O wa lara iko agbaboolu-afẹsẹgba obinrin Naijiria lodun fun idije Ife Adulawo lodun 2004,idije Ife agbaye ti odun 2007,ati idije olimpiki ọdun 2008.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Mercy Ima MacJoe, tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi Mercy MacJoe tí wọ́n bí Níjo Oṣù Kẹfà Ọdún 1993 (June 20 1993) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká fún ipa tó kó nínú sinimá Jenna’ ‘àti Magdalene..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2018, wọ́n yàn án láti díje fún Àmín-ẹ̀yẹ fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olú-ẹ̀dá-ìtàn tó dára jù lọ ti City People Awards bẹ́ẹ̀ ló gbamín ẹ̀yẹ ti Hollywood and African Prestilọ́rọ̀ Awardsfún òṣèré fún lọ́dún 2019.Iṣẹ́ kòsọ bi onísinimá àgbéléwòMercy bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 2011 pẹ̀lú ipa tó kó nínu sinimá lonely Princess pẹ̀lú gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin Mercy Johnson.Lẹ́yìn ìgbà náà ló ti ń kópa nínú oríṣiríṣi sinimá, tí ó sìn di ìlúmọ̀ọ́ká..
wikipedia
yo
Lára àwọn sinimá tí ó ti kópa ni; ọ̀pọ̀ Crew, Zenith of Love, Shame, Bread of Life, Girl Next Door àti alán..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá rẹ̀, ó ti báwọn kópa nínu àwọn sinimá àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Ghana..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2018, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ló wá ẹnu sí i, tí ọ̀pọ̀ sìn gbóríyìn fún un nípa ipa tó kó nínú sinimá Jenna..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2020, bèrè ẹ̀kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ sinimá ti New York Film Academy.Gẹ́gẹ́ bí olóòtú sinimá àgbéléwòlọ́dún 2018, ó ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó pè ní Red, tí wọ́n sìn ṣe àfihàn rẹ̀ ní ìbaka TV, pẹ̀lú àwọn gbajúmọ̀ àwọn òṣèré bíi Nonso Diobi, Ifeanyi Kalu àti Mercy MacJoe, tí ó kópa olú-ẹ̀dá-ìtàn fún ara Reinté..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2019, ó tún gbé àwọn sinimá gbankọgbì mẹ́ta jáde tí àkọ́lé wọn n jẹ́, 30 and Single, ó ya èyí ní London, Love in a puff àti Passion's Promise.Awards and Recognítionate àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀ate àṣàyàn àwọn sinimá àgbéléwò Reìdaríoṣù CrewZenith of Loveẹlẹ́lọ̀ọ́Bread of Lifegirl Next Doorṣètòeselenerebsessed Lọ́dúnd Daniel K DanielWedding Eve Pleasomesome in Hellbody of a Virginmoon Byded by Fate’’àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Florence Kíkẹ́lọmọ Ajayi jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí ó wà nínú Ikọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà nígbà kan rí..
wikipedia
yo
O n gba bọọlu dije fun iko agbabọọlu-afẹsẹgba obinrin dinamo guadalajara ni orilẹ-ede Spain alábala keji.ise Kíkẹ́lọmọ bẹrẹ iṣẹ agbabọọlu-afẹsẹgba fun Ikọ̀ Agba-afẹsẹgba obinrin Naijiria pẹlu kókó Queens, Rivers Angels, Jagede Babes ati Pcancan Stars ni abala idije keji ti obinrin Naijiria..
wikipedia
yo
O dara po mo iko egbe agbaboolu-afẹsẹgba obinrin, niìsọkúsọkirts ti orile-ede Germany leyin ti o kopa ninu awon iko egbe agbabọọlu-afẹsẹgba obinrin Naijiria ninu idije ti 1999 FIFA Women's World Cup..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó padà sí Nàìjíríà, ó sin gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Police FC of Lagos àti Bàtata Queen, kí ó tó tún fò fẹ́rẹ̀ dèrò China, níbi tí ó ti dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbabọọlu-afẹsẹgba obinrin tianjin tẹ́dà (Women) lọ́dún 2008 tí ó sìn díje nínú ìdíje àgbàbuta obinrin wọn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Znk Krka ní Slovenia, pógon Ìdílo ní Poland àti Diamo Guàdátan ní Spain.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mike Ezuruonye ti won bi ni ojo kokanlelogun osu kesan an odun 1982, je osere ori-itage omo orile-ede Naijiria.ibẹrẹ aye ati eto Eko rẹwọn bi Mike ni ilu Uzoakoli ni Ipinle Abia won bi ni ojo kokanlelogun osu Kesan an odun 1982..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Federal Government College, ní ìlú Wikun, ní ìpínlẹ̀ Taraba àti ilé-ẹ̀kọ́ Archbishop Agyy Memorial ní Ìpínlẹ̀ wákọ́ Èkó kí ó tó wọ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Nnamdi Azikiwe láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìṣirò owó..
wikipedia
yo
O sise funyin die nile ifowo-pamo saaju ki o to dara mo ere-itage.o ti kopa ninu awon ere ere-kan, won-kan, won si ti yan an fun ami-eye ti “òṣèrékùnrin ti o peregede julo latari ipa ti o ko ninu eresin Robsin ninu ayeye ti Africa Movie Academy Awards. naa ni won tun ni won tun yan an fun ami-eye ti o peregede julo lati nibi ayeye ti ayeye ti Africa Magic Viewers Choice Awards.Igbe ile re se igbeyawo pelu aya re nkéchi Noro, won si ti ebi okunrin ti won so ni Rey nké ipinle Ezuruonye..
wikipedia
yo
He has a younger sister, chichi, who is a physician in the United Kingdom.Àwọn aṣayan ere rè endless Passion (2005) broken marriage beyond reason Critical decision unforeseen (2005) Occultic Kingdom desire (2008) ropes of Fate (2010) keep me alive (2008) unforgivable (2014) calabash part 1 & part 2 (2014) The Duplex (2015)àwọn ìtọ́kasí àwọn ìtàkùn igbo male Actors Actors Film film Actor ẹ̀nìyàn alààyè-century Nigerian male Actorsmale Actors in Yoruba Cinemandington Azikiwe University alumnimale from Lago Lago Ọjọ́ìbís ni 1982..
wikipedia
yo
Femi Odugbemi tí wọ́n bí ní ọdún 1963 jẹ́ ònkọ̀tàn àti Olùya fọ̀ràn àwọn Àkọsílẹ̀ LÁÉ LÁÉ, adarí eré, olùgbéré jáde àti ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Iṣẹ́ Refemi Odugbemi ni wọ́n bí ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Montana state University níbi tí ó ti kọ́ nípa gbígbé eré àti Isakalẹ̀ ètò orí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Amóhùn-máwòrán ti NTA, lẹ́yìn èyí ni ó tún ṣiṣẹ́ ní Lintas advertising and Mccann-Erickson fún eré orí rédíò .Ó ti kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, ó sì ti ya àwọn fọ̀ràn àkọsílẹ̀ láé láé lóríṣiríṣi, ó sì ti gbé àwọn eré oníṣe ọlọ́kan-ò-jọ̀kan jáde pẹ̀lú.òun ni ó gbé eré oníṣe onípele àtìgbàdégbà ti Tinsel tí ó bẹ̀rẹ̀ ní àárín oṣù kẹjọ ọdún 2008 jáde..
wikipedia
yo
Ó ti fipá rẹ̀ lélẹ̀ ní orí iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùgbé àwọn eré oníṣe orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ní ilẹ̀ Áfíríkà .Òdúmíràn ni ó kó eré Bariga Boys, òun ni ó darí rẹ̀ tí ó sì gbé jáde pẹ̀lú,..
wikipedia
yo
Fọ́nrán àwòrán Bariga Boys jẹ́ ìṣesí àti ìgbé ayé àwọn ènìyàn pàá pàá jùlọ, àwọn òṣèré ojú pópó ní ìlú Bariga ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, òun ni ó kọ tí ó sì ya fọ̀ràn àwọn Àkọsílẹ̀ làẹ̀ là tí ó pe àrírí rẹ̀ ní Literature, language and Literalism nípa gbaju-gbajà ònkọ̀tàn ìwé Ògbójú ọdẹ nínú igbó Irúmole iyẹn Olugbe Daniel o..
wikipedia
yo
Fágúnwà .Ní ọdún 2002, ó di Ààrẹ fún ẹgbẹ́ Àwọn Independent Television Figiníhà Association of Nigeria, tí ó sì kúrò ní ipò náà ní ọdún2006.He is a member of the Advisory Board of the School of Media and Communications, Pan-African University, a Post Training University.Ó gbé eré kan tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Abokú jáde ní ọdún 2008, eré ti níjì Akanni ṣe adarí rẹ̀.The film wọn The Most Outstanding Short film At the Zuma Film Festival held in 2010 and Best ìkọ̀sẹ̀ at the 6th Africa Movie Academy Awards as held on 10 April 2010 at the gloryland Cultural Center in yẹ̀nà, Bàta State, Nigeria.Ni ọdún 2010, oun ati àwọn kan dá irepresent International documentary film Festival Lagos, èyí tí ó gbé àkòrí rẹ̀ kalẹ̀ lé “Africa In self-conversation” kí wọ́n lè ma ṣe àgbéjáde ìtàn ìtàn Áfíríkà láti ọwọ́ àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà.Wọ́n fìwé pèé kí ó wá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ìgbìmọ̀ tí ó ń rí sí ìdí bóyáni lábẹ́ The Academy of motion Picture and Sciences ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2018, ní orílẹ̀-èdè Amél-èdè National film Corporation fún Femi ní àmì-ẹ̀yẹ ti Rock of Fame ní ọdún 2018 fún iṣẹ́ ribiribi rẹ̀ .Ẹ tún le wó tó tó àwọ ọmọ orílẹ̀ Cerelope Ito Olùka film Makest Directors Directors N Anace NFM Pusi screenlon Dramatists and playwright ènìyàn A Alààyè Film-language film Directors from from Lagos Montana State
wikipedia
yo
Báyọ̀ adébọ̀wálé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 1944 jẹ́ akọ ewì, ònkọ̀wé, ọ̀jọ̀gbọ́n, lámèyítọ́, Ésíṣètò ìwé àti olùdásílẹ̀ ilé-ìwé African Heritage Library and Cultural Centre ti o wa ni , Adeyípo, ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
ììbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọn bi adébọ̀wálé si ìdílé bàbá rẹ̀ Àkàngbé adébọ̀wálé tí ó jẹ́ agbe roko bọ́dún dé nígbà ayé rẹ̀ ó keko nílé ẹ̀kọ́ ti oniwe mẹ́wàá ti mọdá tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn, nibi ti ó ti gba ìwé ẹ̀rí ti Wasce ní ọdún 1958, ṣáájú kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti olukọni ti St..
wikipedia
yo
Peter's níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí tí Grade III nínú ìmọ̀ dídáyí ní ọdún 1961..
wikipedia
yo
Ó sì tún wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ olùkọ́ni Onítẹ̀bọmi ti ìlú ède láti keko gbàwẹ̀ ẹ̀rí olukọni ti Grade II ní ọdún kan náà.Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì Ìbàdàn ní inú oṣù kẹwàá ọdún 1971 níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí (B..
wikipedia
yo
A) nínú ìmọ̀ èdè GẸ̀Ẹ́SÌ ní ọdún 1974, tí ó sì ṣe Àgùnbánirọ̀ ní ọdún 1975..
wikipedia
yo
O sise ni ile-ise Western State Public Service Commission gege bi olukọni ṣaaju ki o to di olukọni ni Ile Itaja ti Ijọba (Government Trade Centre), ni Ipinle Oyo.O kawe gboye ikeji ninu imọ ede Gẹẹsi ni ọdun 1978, ti o si dara pọ mọ́ ile-ẹkọ ikọni ti ipinlẹ Oyo gẹgẹ bi olukọni, ṣaaju ki wọn to gbe lọ si ile-ẹkọ Gbogbonìṣe ti Ilu Ìbàdàn nibi ti o ti di Igbakeji Adari Ile-ẹkọ naa ni ọdun 1999 si ọdun 2003, leyin ti o ti kawe gboye omowe ninu ninu imo Litireso ni Yunifasiti Ilorin ni ọdun 1997.Iṣẹ rẹ Báyọ̀ ti tẹ iwe ti o ogorun , o si ri K9 awọn iwe itan miran ti a ti ri The Virgin ni wọn ti lo ninu awọn ere ni orilẹ-ede Naijiria...
wikipedia
yo
Lára àwọn eré tí wọ́n ti lo ìwé 8tan rẹ̀ ni The Narrow Path tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006, lábẹ́ ilé-iṣẹ́ “Maàmìin" Lábẹ́ àṣẹ àti ìdarí gbajú-gbajà òṣèré àti olùgbéré-jáde àti adarí eré Túndé Kelani..
wikipedia
yo
Wọ́n tún lo ìwé ìtàn Báyọ̀ Adewale nínú eré The White Handker.he. SUred lonely Days, a book That Focus on African Culture.Báyọ̀ ti kópa Kàmì-laaka nínú iṣẹ́ Litireso ní orile-ede Naijiria * paa paa jùlọ Black African Literature in English.he also Sred a novel we out of his mind.Ere onitan rẹ̀ rẹ̀ The River goddess ni ó fi gba ami-eye ninu idije descenwas ní ọdún 1972, ewi rẹ̀ tí ó pè ní per náà ni ó gba ami-eye níbi ayẹyẹ Censo- International Poetry Competition in London fún Ilẹ̀ AduIlẹ̀ Awo..
wikipedia
yo
9pọ̀lọpọ̀ Ìwé àpilẹ̀kọ rẹ̀ ni wọ́n ti ṣàmúlò nínú iṣẹ́ ìwádí ìmọ̀ oríṣiríṣi ní àwọn Fásitì oríṣiríṣi.Àwọn ìtọ́kasí14.Nigerian male Novelists From Osun Statatẹniwáyé Malé poetbóyá of Ìbàdàn ShuUniversity of Ìlọrin Facultythe Polytechnic, Ìbàdàn Faculty, AcadémicsYorùbá Writers from Ìbàdàn Ìbàdàn Académics-Century Nigerian Novelists-Century Nigerian pòb-21st-Century Nigerian Novelists-ọmọbìnrin Nigerian pòbts, Librarians Ọjọ́ìbí ni 1944àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Adenike Grange je Minisita Ana fun eto Ilera lorilẹ ede Naijiria lati ọdun 2007 si 2008.aye rẹ ni ibẹrẹADÉNÍKẸ̀Ẹ́ Grants kawe ni ilu Eko ki o to kọja si St..
wikipedia
yo
Francis' College, Letchworth ní United Kingdom láti tẹ̀ síwájú..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó lọ́dún 1958 sí 1964 ní University of St Andrews lórílẹ̀-èdè Scotland..
wikipedia
yo
O sise ni ile-iwosan Dudley Road Hospital ni Birmingham ki o to pada si Naijiria lodun 1965, ti o sin sise ni awon ile-iwosan ni ipinle Eko..
wikipedia
yo
Ó tún padà sí òkè-òkun, United Kingdom lọ́dún 1967, tí ó sin ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Dókítà àwọn ọmọde St Mary's Hospital for Children..
wikipedia
yo
O kawe gboye dipọlọ si ninu imo ilera ọmọde lodun 1969.lodun 1971, o dara po mo Lagos University teaching Hospital, o sin di olukọ ni ẹka-ẹkọ (College of Medicine) , lodun 1978 ni University of Lagos..
wikipedia
yo
Ó di olùkọ́ àgbà lọ́dún 1981,bẹ́ẹ̀ náà ó di ọ̀jọ̀gbọ́n lọ́dún 1995.Àwòrán Grange ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àgbà-nímọ̀ràn sí Ilé-Iṣẹ́ Ètò Ìlera Ìjọba Àpapọ̀, Federal Ministry of Health, Who, UNICEF, Unfpa àti Usaid..
wikipedia
yo
Oun ni oludamọran si ajo who ni Naijiria lori eto ilera omo bibi lati odun 1993 si 1999..
wikipedia
yo
O ti kọ ju ìwé aadọta lọ lórí ètò ìlera, pàápàá jù lọ lórí àìsàn diarrhoeal ati ètò oúnjẹ ẹ̀tọ́ fún ọmọdé..
wikipedia
yo
O je Aare fun egbe International Paesadia Association.lenu ise re, won mo on gege bi àṣegbé fun ilera to peye fun awon omo.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Cynthia Onyedinmanasu Chinasakwukwu Erivo (; tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹjo Oṣù Kìíní Ọdún 1987 jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, olórin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè England, ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ Nàìjíríà FIFA..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ Amin-eye, paapaa ju lo Amin-èye Emmy, Tony, ati Grammy, bẹ́ẹ̀ náà wọ́n ti yàn án fún Academy Awardsibere ayé àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ Wkọ́ Obì Erivo jẹ́ Ọmọ bíbí Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ti wọ́n lọ gbé ní agbègbè Stockwell ní London Orílẹ̀-èdè United Kingdom..
wikipedia
yo
O kawe ni la rẹtrate Roman Catholic girls' School..
wikipedia
yo
Evo bere eko giga Yunifasiti ninu imo ero orin ni University of East London; leyin odun kan ti o bere ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ yii, o kowe lati kopa ninu, won ko o lẹ́kọ̀ọ́ ni Royal Academy of Dramatic artise.Iṣẹ́ Tiata reeri bẹrẹ ise Tiata lodun 2011 ninu ere itage ti won pe ni The UBrellasllas of Cherbourg, bee o koko farahan ninu ero tẹlifísàn ni Englandninu eto ti won pe ni Chewing Gum lodun 2015..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ nínú ipa tó kó nínú sinimá Broadway, The Color Purple láti ọdún 2015 sí 2017, àkọ́kọ́ yìí ló gbamin-ẹ̀ye Tony Award for Best Actress in a Musical ní 2016 àti Grammy Award for Best Musical Theater Album, pẹ̀lú àwọn Àmin-ẹ̀yẹ mìíràn..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sinimá àgbéléwò lọ́dún 2018 nígbà tó kópa nínu sinimá Wiganlle àti Bad Times at the el Royale..
wikipedia
yo
Ẹ̀rívo kópa Harriet Tubman ninu sinimá Harriet lọ́dún 2019, lórí ipa yìí, ó gbamin-ẹyẹ Academy Award fún òṣèrébìnrin tó dára jù lọ àti orin ara ẹni tó dára jù lọ..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2020, Erivo kópa nínu sinimá àgbéléwò tí wọ́n pè ní The Olùwíjì.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mojisola Christianah Adeyeye je onimo nipa oogun ati ojogbon omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari yàn án sí ipò Olùdarí-Gbogbogbo fún ilé iṣẹ́ tí ó n rí sí ìṣàkóso oúnjẹ àti òògùn (National Agency for Food and Drug Administration and Control) ní ọjọ́ kẹta Oṣù kọkànlá ọdún 2017..
wikipedia
yo
Kí ó tó di wípé wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùdarí fún ilé iṣẹ́ yí, òun ni alága àkọ́kọ́ fún ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ lórí Bijí àti ọ̀jọ̀gbọ́n oníjí nípa ìrú, ìmọ̀ ẹ̀kọ́ àti àyẹ̀wò ọjà nípa oògùn ní ilé-ẹ̀kọ́ tí ìmọ̀ nípa oògùn tí ó wà ní Yunifásítì Roosevelt ní Schaumburg, Illinois, níbití ó ti lo ọdún méje..
wikipedia
yo
O tun jẹ ojogbon ti Pharmaceutics and manufacturing fun odun mokanlelogun ni Yunifasiti ilu Duquesne ti o wa ni Pittsburgh, Pennsylvania, orile-ede Amerika..
wikipedia
yo
O tun jẹ olukọni agba Fulbright, Onimọnran ati 2008 American Association of Pharmaceutical Scientists Fellow (ẹlẹgbẹ obinrin Afirika Akoko)..
wikipedia
yo
O tun jẹ Fellow of the Naigerian Academy of Science and Nigeria Academy of Pharmacy..
wikipedia
yo
Awọn iwadi i rẹ ti o nifẹ si wa ni awọn agbegbe ti iṣaaju-agbekalẹ, idagbasoke alakoso akoko ti o lagbara, semisolid ati awọn ọna iwọn lilo n kan olomi, ati ipilẹ IND ati ogbon ti idagbasoke ọja ti o pe..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile ati Alakoso ti Elim ayaẹ Pharmaceuticals Rolling MeṢẹ́gun, Illinois..
wikipedia
yo
Nipasẹ Ile-ẹkọ giga Yunifasiti ilu Duquesne, o se agbende oogun kan ti won n pe ni anti-retroviral (HIV / AIDS) Dece fixed-dose combination and formulation ni orile-ede United Kingdom ati South Africa.Eko Moji Adeyeye lo si ile-eko giga Yunifasiti ilu Naijiria ti o wa ni NST nibiti o ti gba oye ALÁKÒÓKÒ ninu imo nipa oogun (Bachelor's degree in Pharmaceutics) ni odun 1976..
wikipedia
yo
O te siwaju lo si ile-eko giga Yunifásìyí Ilu Georgia nibiti o ti gba oye eleekeji ninu imo oogun (Masters degree in Pharmaceutics) ni odun 1985 ati oye imo ijinle (PhD degree) ni odun 1988 lati ile-eko giga yi kanna.Awon ise e re Moji Adeyeye bere ise re ti o yan laayo gege bi i onimo-oogun ni ile-eko giga Yunifasiti ilu Ibadan, Ipinle Oyo, orile-ede Naijiria ni odun 1976..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti lọ di olórí ní éékà tí ó ń mójútó ìrúkò ní ilé ìwòsàn ti Baptist tí ó wà ní Ogbomosho, ìpínlẹ̀ Oyo, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọdún 1979 sí ọdún 1980..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ-ẹkọ rẹ ni Ile-ẹkọ nipa Oogun eeka ti Yunifasiti ti Puerto Rico, San Juan gege bi i igbakeji ojogbon ni odun 1988, ki o to di wipe o tesiwaju lo si ile-eko giga Yunifasiti Duquesne, ti o wa ni Pittsburgh, Pennsylvania gege bi i igbakeji ojogbon ni odun 1989 ki o to wa gba igbega si ipo ojogbon ni odun 1994 ni ile-eko giga Yunifasiti yi kanna..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2003, o gba igbega si ipo ojogbon nipa imo oogun ati imo-iṣẹ Oogun, eeka ti Imọ-ẹrọ Oogun, Ile-iwe ti Oogun ni Ile-ẹkọ giga Yunifasiti kanna ti o si wa nibẹ titi di ọdun 2010..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí í Ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìmọ̀ nípa oògùn, ìmọ̀-ẹ̀rọ àti ìwàléwá ọjà ìkò, Pagbò ti ìjá òògùn, tí ó wà ní Yunifásítì ìlú Roosevelt, Schaumburg, Illinois títí di ọdún 2018..
wikipedia
yo