cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Scott Ronald Dixon (tí a bí ní Brisbane, Australia, Oṣù Keje ọjọ́ 22, Ọdún 1980), tí a pè ní Iceman, jẹ́ oníwo ọkọ̀ ìga ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìlú Niu Siijù tí ó ngba lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Indy series..
wikipedia
yo
Òun ni aṣaju ti àwọn àkọ́kọ́ 2003, 2008, 2013, 2015, 2018 àti 2020 pẹ̀lú ẹgbẹ́ Chip ganassi Rcing.Ìtọ́kasí.Àwọn ọ̀nà àkòyà ìtaòṣìṣẹ́ ààyè..
wikipedia
yo
Susan Peters tí wọ́n bí lọ́gbọ̀n ọjọ́ Oṣù karùn-ún Ọdún 1989 (30 May 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà tí ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àmin-ẹ̀yẹ tí ó ju ààdọ́ta lọ..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ gbajúmọ̀ atọ́kùn orí tẹlifísàn, afọ̀gé-sójú, atúnnulẹ́sẹ àti aṣerunlóge..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2011, wọ́n yàn án fún àwòrán ìbẹ̀rẹ̀ ti ìwé-ìròyìn olóṣooṣù àṣà àti iṣẹ́ ti oṣù kejìlá..
wikipedia
yo
Olóòtú said Zzen Magazine, Ọ̀gbẹ́ni Arinze nwọkọ̀lọ, júwe báyìí "....
wikipedia
yo
Jùmọ̀kẹ́ Akíndélé jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ agbẹnusọ nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Òǹdó.Ìgbésí-ayé rẹ láti ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Jùmọ̀kẹ́ ní ìlú òkìtì-pupa, ní ìpínlẹ̀ Òǹdó lápá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà.Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní St..
wikipedia
yo
John's Primary School ní òkiti-pupa kí ó tó tẹ̀ síwájú ní St..
wikipedia
yo
Louis Girls Secondary School, Òndó fún ẹ̀kọ́ gíga àti ìwé-ẹ̀rí West Africa School Certificate in 1981..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin láti Obafemi Awolowo, ní ilé Ife tí ó sìn ṣiṣẹ́ amòfin fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó di òṣèlú lọ́dún 2006.iselu rẹ̀Jùmọ̀kẹ́ dí lọ́pọ̀ ẹkùn ìdìbò ògé-pupa II, ṣùgbọ́n kó wọlé..
wikipedia
yo
O tun dije pada lọ́dún 2011, ori ba a ṣe e, o sin wọle..
wikipedia
yo
Àsìkò yìí ló jẹ́ agbẹnusọ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Òndó.Wọ́n yàn án ní agbẹnusọ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Òndó lọ́jọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2015,lẹ́yìn ikú agbẹnusọ àná, Samuel Adésínà tí ó kú lójijì..
wikipedia
yo
Jùmọ̀kẹ́ ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ agbẹnusọ ilé Ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Òndó.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọlásúnsún rẹ̀hanat Alonge (bíi ní ọjọ́ kejì, osù kẹfà odún 1988) tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Súnkànmí jẹ́ olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Súnkànmí gbajúmọ̀ ní ọdún 2015 fún orin for Body tí ó gbé jáde..
wikipedia
yo
Súnkànmí lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Olabisi Onabanjo University níbi tí ó ti gboyè jáde nínú ìmọ̀ Geophysics.ní ọdún 2015, wọ́n yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Most Promising Act to Watch láti ọ̀dọ Nigeria Entertainment Awards..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, wọ́n yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ eléré titun láti ọ̀dọ Sewed All-Youth Award, fashionable Revelation artist of the Year láti ọ̀dọ Lagos Fashion Award àti Upcoming Female Music Artiste láti ọ̀dọ ELOY Awards.Àṣàyàn àwọn orin àkò Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Taiwo Olayemi Elufioye je onimo ogun ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
O si ṣe gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ pẹ̀lú ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O jẹ ikan laarin awon onimo ni ile eko giga ti University of the Sciences ni Philadelphia.O gba owo nla lati odo MacArthur Foundation lati le se oriṣiriṣi ayẹwo lori awon oun ogbin ti o wa ni Naijiria ti o le se iwosan fun awon arun.Ni odun 2014, oun pelu awon obinrin mẹrin jo gba ami eye early career women Scientist in the developing World lati odo elsevier foundation awards.Iṣẹ re Elufioye gba owo lowo MacArthur Foundation lati sise iwadii lori oriṣiriṣi egbò-igi orile-ede Naijiria, lati le ṣayẹwo arun kan, ati lati wá ojútùú si.Ni ọdun 2014, Elufioye jẹ okan lara awon obinrin ti won gba ami-eye ti elsevier foundation awards for early career women Scientists in the developing World..
wikipedia
yo
Elufioye gba ami-eye fun iṣẹ rẹ lori iṣẹ iwosan awon egbò-igi ti orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Iṣẹ iwadii rẹ dalẹ́ lori awọn ohun ti wọn le fi ṣe iwosan fun aisan maleria, egbò, Oyerira, ete ati arun jẹjẹrẹ..
wikipedia
yo
Àmì-ẹ̀yẹ ti Elvier foundation ni wọ́n fún yaiwo ní ayẹyẹ American Association for the Advanment of Science (A-A), láti ipade ọdọọdún wọn ní Chicago, ó sì tún gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbun àti $5000..
wikipedia
yo
Nígbà tó gba àmì-ẹ̀yẹ náà, ìkejì àárẹ̀ ti Yunifásitì ìlú Ibadan, Isaac Adewole, sọ pé àṣase Elufi maa jẹ́ ìwúrí fún àwọn obìnrin mìíràn nínú iṣẹ́ sayensi, àti pé ó jẹ́ ẹni ẹyẹ ti orílẹ̀-èdè Nàíjíríà àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ní ilé Adupọ̀ láèyà.Wọ́n ti ṣagi Elufi ní African Journal of Biowe Research, pharmaco, the Áì, The International Journal of Pharmaceutics, àti African Journal of Traditional, àbí lílò iyì and acetylES.
wikipedia
yo
Tẹjúmade Alakija (Bii ni ojo ketadinlogbon osu karun-un odun 1925) je oṣiṣẹ ijoba ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun si ni obinrin akọkọ ti o ma jẹ olori fun awọn oṣiṣẹ ijọba ni ipinlẹ Oyo.baba tẹ́júmade jẹ ọba ni Ilu Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Oxford University, ó sì gboyè jáde gẹ́gẹ́ bí olùkọ́..
wikipedia
yo
O gboye pro-Chancellor fun ile eko giga ti University of Abuja lati odun1993 1993titi di odun 1997..
wikipedia
yo
Alakija ku ni odun 2013 ni ile iwosan University College Hospital ni iluIbadan.Awon jipo..
wikipedia
yo
Temi lọlá Balogun tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ Suyfún jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun si ni olugbe silẹ eto Skinny girl in Transit.O lọ si Ile Eko Queen's College ni Ilu Eko..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Nottingham Trent University..
wikipedia
yo
Òun àti àbúrò rẹ̀ jọ kọ́ orin Soyinka's Afro ní ọdún 2009.Balogun di atọ́kùn fún ilé iṣẹ́ Cool FM ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
O gbe ere Things Men Say jade ní ọdún 2017.Ní ọdún 2019, òun àti N6 jọ ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ fún olórin Cardi B nígbà tí ó wá sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Tèmi jẹ́ ìyàwó fún tìmí Akintúààbọ̀, wọ́n sì ti bi bi ọmọ meji.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Títí Adélagún Oyinsan (bíi ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù kẹjọ ọdún 1985) tí orúkọ ìnági rẹ̀ jẹ́ títíthesọ́nàte jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ atọkun fun eto wake up Naijiria ni ile ise TVC..
wikipedia
yo
Òun sì ni atọ́kùn ètò Jerohamumith, èyí tí wọ́n gbé kalẹ̀ fún àwọn ọmọdé, kí wọ́n ba le mọ èdè gẹ̀ẹ́sì dáadáa.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí títì sí ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí orílẹ̀ èdè England nígbà tí ó ṣì wà ní ọmọdé, ó sì wà ní ibẹ̀ fún ọdún mẹ́wàá..
wikipedia
yo
O lọ si Ile Eko Queen's College ki o to te siwaju si Ile Eko giga ti University of Lagos lati kẹkọọ ede Gẹẹsi.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Bola Agbaje ti won bi lodun 1981 je gbajumo onkowe ere-onise omo Naijiria..
wikipedia
yo
Ilu London ni awon obi re ti won je omo Naijiria bi i Síroko reere-onise akoko ti Agbaje ko ni Gone too Far!, won gbe e jade ni Royal Court Theatre ni London, nibi ti o ti gba amin-eye Laurence Olivierfun ara ọ̀tọ̀ ise Tiata ..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ṣe atunjáde rẹ̀ ní ránpé ní' Albany Theatre àti Hackney Empire.Agbaje náà ló tún kọ eré-ONÍṢẸ́, The burial.Lọ́dún 2018, wọ́n Agbaje gẹ́gẹ́ bí ọkàn nínú àwọn ogoji, tí ọjọ́ orí wọn kò jù ogójì lọ, tí wọ́n yàn ní Royal Society of Literature lati Dẹ́kun àlàfo ìtàn.Ìgbésí-ayé ara rẹ̀Agbaje sọ pé òun Gbàgbọ́ nínú Ọlọrun ṣùgbọ́n òun kò ní ìgbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn ọmọ-lẹ́yìn JÉSÙ tàbí Musulumi..
wikipedia
yo
Abimbola ÀlàóAbimbola gbémi Àlàó, tí a tún mọ̀ sí àbí Àlàó, ó jẹ́ Olùṣọ́tan, Òǹkọ̀wé, atúmọ̀ ìwé àwọn ọmọ kékeré àti Olùwídìí.Ìgbésí Ayéàbí Abimbola sí ìlú Ìbàdàn, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O kẹkọọ ni University of Ibadan, Nigeria, nibiti o ti gba ba (Hon) Classics ni 1988 ati ma Classics ni 1991..
wikipedia
yo
O ti kọ oriṣiriṣi ewi, itan kékèèké àti eré oníṣe..
wikipedia
yo
Ni 2008, ere onise re, 'Legal Stuff', yege BBC and Royal Court Theatre '24 degrees' Writing competition..
wikipedia
yo
Ni 2007, a yan gegebi oluko ni creative writing at the University of St Mark & St John (MarJon), Plymouth, nibiti o ti koni fun odun mokanla..
wikipedia
yo
Olùgba Plymouth's 2017 Mayflower scholarship, nísinsìyí ó ń ṣèwádìí nípa influence of sychoSocial intervention on disease progresSi in people living with dékópaa.Abimbola jẹ́ olukọni àti olùpèsè fun'story*'Weas for Depadea', a special study unit (sSU) in Medical humanities, at the Peninsula school of medicine and hisstry, Plymouth..
wikipedia
yo
The program, developed by Abimbola, explores Non-57:ological approach to dékópaa care..
wikipedia
yo
Ohun ni a fún àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé pẹ̀lú oríṣi àjẹsáradémẹ́ńtìa..
wikipedia
yo
Ni 2015, Abimbola darapọ mọ Alzheimer's Society lati dari 12-Week Project with Service ọdúnthe Memory cafes..
wikipedia
yo
Ó tún kópa sí 'Saturday thought', a Weekly column in the Herald.Ami Ẹyẹ 2005, BBC 'B"Z' Burmudic Award[5]2008, BBC/Royal Court Theatre ’24 degrees' Writing competition.[6] performanceSabimbola performs storytelling,[7] Radio Musicals [8] and Poetry on Stage..
wikipedia
yo
(2005) mantra lingua.My Talking dictionary & Interactive CD Rome' Yorùbá & English – Yoruba Translation by Abimbola Àlàó..
wikipedia
yo
(2005) mantra lingua.Referencesnígbàtí "Parhelikaintary glory for World Stories"
wikipedia
yo
Retrieved 30 October 2013.wàrà "Digital Heroes rẹ́gíonal Winners"
wikipedia
yo
Retrieved 30 October 2013. "Dekọ́dòkàn story-telling is àwésome"
wikipedia
yo
Retrieved 24 May 2014.276 "National award for démẹ́ńtìa project"
wikipedia
yo
Retrieved 24 May 2014.Benin "The Cool breeze is now blowing"
wikipedia
yo
Retrieved 10 September 2011.Use "Dear Toríọ̀la, Let's Talk About Aperimemeric By Abimbola....
wikipedia
yo
She studied at the University of Ìbàdàn, Nigeria, where she Gained a ba (Hon) Classics in 1988 and an ma Classics in 1991..
wikipedia
yo
She has also written numerous Poems, short Stories and plays..
wikipedia
yo
In 2008, Her Short Play, 'Legal Stuff', won the BBC and Royal Court Theatre ’24 Degree' Writing Competition..
wikipedia
yo
In 2007, she was appointed as a lecturer in creative writing at the university of st mark & St John (MarJon), Plymouth, where she taught for 11 years..
wikipedia
yo
A recipient of Plymouth's 2017 Mayflower scholarship, she is currently reseclusi the influence of sychoSocial intervention on disease progression in people living with dékópaa.Abimbola is a visiting lecturer and lead ìbéèrèder of 'storylẹ́hìn for Depadeláyàa', a special study unit (sSU) in medical humanities, at the Peninsula school of medicine and histàbí tíṣà..
wikipedia
yo
It is offered to people who live with various forms of démẹ́ńtìa..
wikipedia
yo
In 2015, Abimbola Collaborated with the Alzheimer's society to run a 12-Week Project with Service ọdúnthe Memory cafes..
wikipedia
yo
She also Congbáà to ‘Saturday thought', a Weekly column in the Herald.Awards, BBC 'Breez' Burmudic Award[5]2008, BBC/Royal Court Theatre ’24 Degree' Writing competition.[6] performanceSabimbola performs storytelling,[7] Radio Musicals [8] and Poetry on Stage..
wikipedia
yo
In 2008, Her Short Play, 'Legal Stuff', won the BBC and Royal Court Theatre ’24 degrees' Writing Competition..
wikipedia
yo
A recipient of Plymouth's 2017 Mayflower scholarship, she is currently reseclusi the influence of sychoSocial intervention on disease progression in people living with dékópaa.Abimbola is a visiting lecturer and lead ìbéèrèder of 'storylẹ́hìn for Depadeláyàa', a special study unit (sSU) in medical humanities, at the Peninsula school of medicine and histry, Plymouth..
wikipedia
yo
It is offered to people who live with various forms of déaibikitaa..
wikipedia
yo
She also Con73 to 'Saturday thought', a Weekly column in the Herald.Awards,2005, BBC 'Bree' Burmudic Award[5]2008, BBC/Royal Court Theatre ’24 Degree' Writing competition.[6] performanceSabimbola performs storytelling,[7] Radio Musicals [8] and Poetry on Stage..
wikipedia
yo
(2005) mantra lingua.My Talking Dictionary & Interactive CD ROM' Yorùbá & English - Yoruba Translation by Abimbola Àlàó..
wikipedia
yo
Máyọ̀wá Adegbile tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá Oṣù kẹ̀sán Ọdún 1986 jẹ́ gbajúmọ̀ àfọwọ́ṣàánú ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn ọmọ Nàìjíríà mẹ́ta tí wọ́n yàn mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọ́n ní Áfíríkà fún àṣeyọrí ìdíje Google lọ́dún 2014..
wikipedia
yo
Máyọ̀wá kọ́kọ́ lo ìkànnì YouTube láti ṣe ìkówójọ fún ilé-iṣẹ́ àfọwọ́ṣàánú rẹ̀, Ashake Foundation, èyí tí ó dá sílẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́ àwọn abiyamọ opó, ó máa n fun wọn ní irinṣẹ́ láti ṣòwò jẹun àti láti ran ebili wọn lọ́wọ́.Ilé-iṣẹ́ àfọwọ́ṣàánú, Ashake (Foundation) Máyọ̀wá bẹ̀rẹ̀ Ashake Foundation, ilé-iṣẹ́ àfọwọ́ṣàánú fún àwọn abiyamọ ọ̀pọ̀ lọ́dún 2012 pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ fún méjìlélógún ọ̀pọ̀ àti àwọn ọmọ mẹ́rìndínlógójì, tí ó pèsè ìrànlọ́wọ́ owó àti ohun èlò okòwò fún..
wikipedia
yo
Èyí ti mú kí púpọ̀ nínú kúrò nínú iṣẹ́, tí ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ sin padà sí ilé-ìwé .àwọn Àmin-ẹ̀yẹ Máyọ̀wá gba Àmín-ẹ̀yẹ tí Junior Chamber International Lóṣù Keje ọdún L 2017, gẹ́gẹ́ bi ọ̀kan nínú àwọn ọmọde mẹ́wàá lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n Moke nínú afowo adarí ọfẹ.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Alanana Nwigwe je osere ori-itage ati olùgbéré-jade omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti ìlú Calabar ní ìpínlẹ̀ Delta nínú ìmọ̀ ìṣúná.Iṣẹ́ rẹ̀ ńwígwe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lásìkò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ Modeeli pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Runway àti Print Model ṣááju kí ó tó darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà..
wikipedia
yo
O gbe ere kan jade ti o pe ni Seroki Change Change Ere ti Jẹitan Ọdò dari rẹ ni ọdun 2004..
wikipedia
yo
Ní báyìí, ìpawe n lọ sí ìlú Los Angeles àti orílẹ̀-èdè Nigeria láti ṣiṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ti kópa nínu àwọn eré oriṣiriṣi ṣááju kí ó tó kópa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Black November tí àwọn òṣèré bíi Kim Basinger, Mils Rourke, Vvca a..
wikipedia
yo
Fox, Akon, Wyclef Jean, and Anne heche ti kópa ní ọdún.Ó kópa bi olú-ẹ̀dá ìtàn gẹ́gẹ́ bi paito nínú eré Hell or High Water, ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn eré yí ni ó pinu láti máa kópa nínú eré tí ó bá ti níṣẹ́ pẹ̀lú ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ.Ní ọdún 2017, News of Africa pèé ní ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn Méjìlá tí ojú wọ́n fani-mọ́ra jùlọ ní Nollywood, lọ́dún náà.Àwọn eré rẹ̀àwọn eré orí amojì-máwòrán àmì-ẹ̀yẹ àti ÌFISỌRÍ rẹ̀ wọ́n yàn ńwígwe àmì-ẹ̀yẹ ti Nollywood and African Film Critics Award, ní ọdún 2015, àti òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ African Oscars nínú eré Black November.Ní ọdún 2016, wọ́n tún yàn án fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ nínú eré Gẹ̀ẹ́sì níbi àmì-ẹ̀yẹ City People Entertainment Awards.Àwọn ìtakùn àtiàwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1982 Mago Actors From From Imo State-21st Nigerian Maẹbọ Actor of Calabar Aludọ́gba Ènìyàn Alààyè Film Actors Actors National..
wikipedia
yo
Titilope Gbemisola Aiku ti gbogbo eniyan mo si títọlope akosa je agbejoro ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ títí akọsa & Co ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó jẹ́ agbẹnusọ fún àwọn obìnrin lórí ètò tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ towards a Gender responsive Green Clímate Fund in Africa ní ibi ayẹyẹ Paris Clímate treaty.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí títí sí ìlú Èkó, ibẹ̀ sì ni ó dàgbà sí..
wikipedia
yo
O gboye ninu imo ofin lati ile eko giga ti Lagos State University, o si te siwaju si ile eko giga ti University of Lagos nibi ti o ti gba Masters re.Iṣẹ Akosa da ile ise tire ti o pe ni titi akọsa & co pelu awon elegbe re miiran, oun si ni olori ati olukọni onimoran nipa ofin fun Ile iṣẹ naa.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Titilope Funsọnu, ẹni ti àwọn èèyàn mọ̀ sí titi sọnuga, jẹ́ akéwì, Ẹngi, àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Wọn bíi si ìlú Èkó, ó sì lọ sí orílẹ̀ èdè Canada nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́tàlá..
wikipedia
yo
O sise fun odun marun-un gege bii Ẹn.Ni odun 2011, o gba ami eye onkowe tuntun lati odo Canadian authors Association..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó gbé ìgbà orókè níbi ìdíje Maya Angelou Poetry Contest..
wikipedia
yo
Ni osu karun-un odun 2015, o di akewi akoko ti o ma farahan nibi ayeye ti won fi gbe aare orile ede Naijiria sori oye..
wikipedia
yo
Funsọnu ti kéwì níbi ayẹyẹ Lagos International Poetry Festival.Yato si ewì, Dsọnuga ti kópa nínu eré ṣíṣe..
wikipedia
yo
O ko ipa Eki ninu ere gidi Up pẹlu awọn oṣere bii OC dira, DeYemi kèfèrí, Somke Iyamah ati Ikechukwu onunaku..
wikipedia
yo
O je ambase fun she will Connect program ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
O ko orin 'Ada 'Ada The Country'ni'.Ni ọdun 2015, o se ikede igbeyawo rẹ pẹlu ayaworan ti orukọ rẹ jẹ ṣeun Williams.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Eniwa Ajayi jẹ́ agbẹjọ́rò ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ni arun cerebral palsy.ibẹrẹ pepe aye ati eko re Ajayi ni omo kerin láàarín awon omo marun-un ti awon obi re bi..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ kò kọ́kọ́ fẹ́ ran lọ sí ilé ẹ̀kọ́ nítorí Àìlera tí ó ní..
wikipedia
yo
Àìlera yí kọ́ fún ni àǹfààní láti lè jókòó, dúró tàbí rìn..
wikipedia
yo
O gboye giga jade lati ile eko giga ti University of Helrtfor2009 ninu imo ofin agbaye.Iṣẹ o bẹrẹ iṣẹ ni mobility aid and appPadani research and development center..
wikipedia
yo