cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O kọkọ wun un ko kawe gboye ninu imọ iṣẹgun òyìnbó ni Glasgow University ṣugbọn o wa papa lọ kawe gboye ninu imọ ayika ni London School of Economics.. | wikipedia | yo |
Ni kété tó padà sí Nàìjíríà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alámòójútó ní ilé iṣẹ́ adájọ́ ní ìpín Èkó.. | wikipedia | yo |
Ni àsikò rẹ̀, ó ṣe ìdásílẹ̀ Ilé-ẹjọ́ àwọn màjèsín àti ẹgbẹ́ àwọn ọmọbìnrin ní ìpínlẹ̀ Èkó, bẹ́ẹ̀ ló ṣe ìrànlọ́wọ́ láti ṣe ìdásílẹ̀ British leprosy Relief Association ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1949, ó tún padà sí òkè-okun láti kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin tí ó sìn di amòfin lọ́dún 1953.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà, ó dá ilé iṣẹ́ sílẹ̀ pẹ̀lú Gloria Rhodes, bẹ́ẹ̀ náà lọ́ ṣiṣẹ́ John Idowu CONMArad Taylor.. | wikipedia | yo |
Nígbà tó yá, ó tún lọ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alámójútó àwùjọ, òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó di ipò yìí mú ní Nàìjíríà.Ó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá ilé iṣẹ́ ìfọpo MoBil lọ́dún 1957.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1961, Momas gba iṣẹ́ ìfọpo ní Nàìjíríà lọ́dún, wọ́n sin fi í ṣe ọ̀gá yányán níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1967, ó di akọ̀wé àgbà olùdarí Àjọ Àwọn Oníṣòwò káràkátà ti Ìpínlẹ̀ Èkó, Lagos State Chamber of Commerce.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1961 sí 1965, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára aṣojú Nàìjíríà ní Àjọ Àgbáyé United Nations.Àdùkẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ New Era Girls College, tí ó jẹ́ ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ International Women Society of Nigeria àti ọmọ ẹgbẹ́ sọ̀rọ̀ptimist International.Wọ́n fún ní oye digírì ní Barnard College.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Doris Simeon je osere fiimu ede Geesi ati Yoruba ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Edo ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti Èkó rẹ̀ wọ́n bi Simeon sí Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti péft Institute níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Production Management.IṢẸ́ Ó kópa nínu eré Efe ti Papa Ajasco.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó darí nínú eré gbàtá Dreamz gẹ́gẹ́ bi olólùfẹ́ dá Grin.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu oríṣìíríṣìí àwọn eré bíi olójú ède, Alakadá, Ten Million Naira , Moja témi àti Eti kẹta.yàtọ̀ sí eré ṣíṣe, Simeon ma n ṣe alága ìdúró àti atọ́kùn ètò lóri Oripé.Ẹ̀bùn ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ìbílẹ̀ tó dára jù lọ láti ọ̀dọ AMAA ní ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ibilẹ̀ tó dára jù lọ láti ọ̀dọ́ ZAFAA Award fún ipa tí ó kó nínu eré àṣírí.. | wikipedia | yo |
Awon ami eye ti o tun ti gba ni Award for Excellence lati odo Okpella Movement ni ile United States, Best Indigenous Artist lati Odò Apesọ́nà Development Group ati 2015 All youths Tush Awards Ayta Role Model (Movie) Award.Igbeyawo o fẹ́ Daniel Ademinọkàn, won si bi ọmọkunrin kan ti oruko re je David.. | wikipedia | yo |
Oun ati ọkọ rẹ pinya ni Oṣu Karun-un ọdun 2013.àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Olusola AdeJoke David-Borha jẹ́ olùdarí àgbà fún ilé ìfowópamọ́ Standard Bank ti ilẹ̀ Áfríkà láti ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
O je oludari agba fun Stanolónìí IBM Holdings titi di osu kìíní odun 2017.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ adarí fún ẹgbẹ́ Nigerian Economic Summit Group láti ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ awọn adari IBMC ni Oṣu Keje ọdun 1994.. | wikipedia | yo |
O je ikan laarin awon adari fun coca-cola hBC AG lati ọdun kefa odun 2015.. | wikipedia | yo |
O jẹ ikan laarin awon adari ni ile eko giga rẹdee's University.ibẹrẹ pẹpẹ ayé ati eko rẹ won bi David si ilẹ Accra ni orile ede Ghana.. | wikipedia | yo |
Ó padà sí Nàìjíríà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlá.. | wikipedia | yo |
O gboye jade lati ile eko giga ti University of Ibadan ninu imo Economics ni odun 1981.O je omo egbe Chartered Institute of Bankers of Nigeria.Iṣẹ David-Borha bẹrẹ ise ni Ile ifowopamo ti nal Merchant Bank lati odun 1984 titi di odun 1989 ki o to wa darapò mó ile ifowopamo IBM | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007, ÌBMC àti Stanctif Bank Group parapọ̀ láti di Stanctif IBt Holdings, Sola sì jẹ́ ìkan láàrín àwọn olùdarí wọn.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kìíní Ọdún 2017, ó gba ipò olùdarí àgbà fún Standard Bank Group.Ó jẹ́ adarí fún CRgi Services Credit Bereau PLC àti University of Ibadan Business School.Ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi oníṣòwò bìnrin fún ilẹ̀ West Áfríkà àti Afrika láti ọ̀dọ All Africa Business Leaders Award.Sola jẹ́ ìyàwó fún David-Borha, wọ́n sì ti bí ọmọ mẹ́ta.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Aikuda Olaji je olukọ ninu imo ofin ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Òun sí olórí ẹgbẹ́ Nigerian Association of Law Teachers àti VV fún ilé ẹ̀kọ́ gíga ti afẹ́ Babalola University.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1995, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú UNICEF.I Arabinrin Ọlárìndé ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ ìmọ̀ òfin fún ọdún tí ó ti lé ní ọgbọ̀n.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀gbẹ́ think tank èyí tí wọ́n dá fún abo àwọn ọmọdé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yo.. | wikipedia | yo |
Oun si ni adari fun ẹgbẹ International Federation of Women Lawyers.. | wikipedia | yo |
Ọmọ rẹ, Ìfẹ́dayo Olarìndé jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí radìío Cool FM.Awon ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
somke Iyamah iddmas je osere ati modeli ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmò fún ipa tí ó kó nínú àwọn eré bíi 93 Days, The Wedding Party, The ẹ̀sìntion, àti gidi Up.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Somke sí ìlú ìkà ní ìpínlẹ̀ Delta.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ ni Andrew ati Edomu ìyámah tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ìlú Ìkà (AGBOR).. | wikipedia | yo |
Oun ni ọmọ kẹta ninu àwọn ọmọ mẹrin tí àwọn òbí rẹ̀ bí.. | wikipedia | yo |
Olùkọ́ rẹ̀, Mrs abẹ́ ni ó kọ́kọ́ kọ bí wọ́n ń ṣe jọ àti bí wọ́n ṣe ń ṣe eré.. | wikipedia | yo |
Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti McMaster University nínu ìmọ̀ Biochemistry.Iṣẹ́ ò kópa nínú eré 93 Days gẹ́gẹ́ bí dókítà kan tí ó kó àrùn Ebola.. | wikipedia | yo |
Ipa tí ó kó nínú eré yìí ló fà tí ó fi gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ láti ọ̀dọ ELOY Award.Ó jẹ́ AmBasedo fún ilé iṣẹ́ Multichoice Nigeria.Òun ni ó ṣe aṣojú fún ilé iṣẹ́ Andrea Iyamah tí àbúrò rẹ̀ gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ìyàwó fún Aaron Iddmáa àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Sophie Bọ́sẹ̀dé Olúwọlé (bíi ní ọjọ́ Kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935) tí orúkọ ìnági rẹ̀ jẹ́ Akóní jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma gboyè jáde nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí Sophie ní ọjọ́ Kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935, ó sì jẹ́ ọmọ ìlú Edo.. | wikipedia | yo |
O lọ si ile eko giga ti University of Lagos nibi ti o ti gboye ninu imo philosophy.. | wikipedia | yo |
Stella Chineyelu ọkọli (Bii ni ọdun 1944) jẹ onisegun ati oniṣowo ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ Emzor Pharmaceuticalìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Stella sí ìlú Kano sí ìdílé Felix Ebelechukwu àti Margaret Modebẹlú tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ìrán Nnewi ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ ẹkọ rẹ ni All Saint Primary School ni ọdun 1954 ni Ilu Onitsha ki o to wa lọ si ògidì Girls Secondary School.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1969, Stella gboyè jáde nínú ìmọ̀ Pharmacy [[ láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Bradford.Iṣẹ kí ó tó dá ilé isẹ́ Emzor Kale, ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé ìwòsàn bíi Middlesex Hospital, Boots The Chemists Limited àti Pharma-De..ko.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù kìíní ọdún 1977, ó dá ilé iṣẹ́ Emzor Pharmaceutical kalẹ̀, ó sì pèé ní Emzor Chemist's limited.. | wikipedia | yo |
Leyin iku omo re Chike okoli ni odun 2005, o bere egbe Chike okoli Foundation ni odun 2006, ti egbe naa si ma n doju ija ko ise ati arun.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Stella Jane Thomas (bíi ní ọdún 1906) jẹ́ agbẹjọ́rò ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni obinrin akọkọ ti o jẹ adajọ ni orile ede Naijiria.ibẹrẹ pẹpẹ aye ati Eko rẹ wọn bi Stella ni ọdun 1906 si Ilu Eko, o si jẹ ọmọ Peter John Claudius Thomas.. | wikipedia | yo |
Baba rẹ̀ ni ọmọ ilẹ̀ Áfríkà àkọ́kọ́ tí ó ma jẹ́ adarí fún Lagos Chamber of Commerce.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Annie Walsh Memorial School ní ìlú Freetown ní orílẹ̀ èdè Sierra Leone.. | wikipedia | yo |
O gboye ninu imo ofin lati ile eko giga ti Oxford University.Iṣẹ Thomas ni obinrin akọkọ lati ilẹ Afrika ti o ma se agbejoro ni Ilu Britain ni odun 1933.. | wikipedia | yo |
Oun si ni obinrin akọkọ ti o ma jẹ Agbẹjọro ni West Afrika.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1943, o di adajọ binrin akọkọ ni West Africa ni ile ejo ti o wa ni Ikeja.. | wikipedia | yo |
Kyle míyàta Larson (bi ni Sawarosh, California, on July 31, 1992) jẹ́ ẹ̀yà American Ọ̀jọ̀gbọ́n ìṣáré ti Japanese Ayalu ti o Anas ninu àwọn Nascar Cup series.Larson darapo Chip ganassi Rcing ẹgbẹ́ láti 2014 àkọ́kọ́ tó àwọn ìbẹ̀rẹ̀ ti 2020 àkọ́kọ́ pẹ̀lú ọkọ ayọkẹlẹ nọmba 42.. | wikipedia | yo |
O ti daduro lati odo awon osise Nascar ati lẹhinna yọ kuro ni ẹgbẹ ganassi ni Oṣu Kẹrin ọdun 2020 nitori iṣẹlẹ ti oro elẹ́yàmẹyà ni ìjẹ ti foju kan.nascar da ipo Larson pada ni Oṣu Kẹwa Ọdun 2020.. | wikipedia | yo |
Bíbẹ̀rẹ̀ akoko 2021, ó sáré ní ẹgbẹ́ Hendrick Momoṣòroports pẹ̀lú nọ́ḿbà ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ 5.Ìtọ́kasí nínú ẹ̀rọ-ayélujára Official site.. | wikipedia | yo |
Margaret Etim ti wọ́n bi lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kọkànlá ọdún 1992 jẹ́ asare ọmọ Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ ninu eré ìwọ̀n irínwó mita 400 metres .. | wikipedia | yo |
O gba amin-ẹyẹ lọ́dún 2010 ninu idije agbaye àwọn ọmọdé, yàtọ si àwọn àmìn-ẹyẹ tí o dìjọ gbá pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ nínú ìdíje eré gbagigbagi 4 × 400Idije tí o ti yara jù ní ti èyí tí o waye ní olúdò lọ́dún 2010, tí o gba a ni iṣẹju-aaya 51.24.Àwọn àṣeyọrí onífaradà rẹàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
AdeJoke Lasisi je gbajumo Soat, àṣegbé imototo Ayika ati onise-ona ọmọ Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile ile-iṣẹ, Planet 3r tí wọ́n máa ń tún àlòkù Ike àti di ohun elo tuntun mìíràn.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2020, AdeJoke gba Amin-eye ti MSme of the year Award, an event which was well attended by state governors and Minits.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Jimmie Kenneth Johnson (bí ní el Cajon, California, September 17, 1975) jẹ́ ẹ̀yà American Ọ̀jọ̀jọ̀ ọkọ̀ ìga ìsáré.Johnson dún nínú NasCar Cup series lati àkókò 2002 sí 2020 pẹ̀lú ẹgbẹ́ Hendrick Mokatars.. | wikipedia | yo |
jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ẹ̀sìn ọmọ-lẹ́yìn-jésù ọmọ bíbí ìlú ifọ̀n, ìjọba ìbílẹ̀ ọ̀sẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ bíbí òjíṣẹ́ Ọlọ́run, Oluwafẹmi ìgbẹ́kẹ̀lé, ṣùgbọ́n tí ó gbé lọ́dọ̀ òjíṣẹ́ Ọlọ́run mìíràn tí orúkọ wọn ń jẹ́ Àpọ́sítélì J.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ iṣẹ orin kikọ lodun 1996, bi o tile je pe lati omo odun mẹrin ni o ti nifee si orin kiko.. | wikipedia | yo |
Ó ti gba àmìn-ẹ̀yẹ nínú iṣẹ́ orin yìí.Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Esther sí orílẹ̀-Iganmu ní ìpínlẹ̀ Èkó, sí ìdílé Olùṣọ́ Àgùntàn, Oluwafemi ìgbẹ́kẹ̀lé àti aya rẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nípa dídara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin ilé-ìjọsìn wọn nígbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́fà.. | wikipedia | yo |
Esther bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà ní ilé-ìwé Central Primary School, ní orílẹ̀-Iganmu ní Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Bákan náà, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Lagos African Church Grammar School, ni ìfako-Ijaye ni Ìpínlẹ̀ Èkó Bákan náà.Àtòjọ àwọn àṣàyàn orin rẹ̀ wẹ́ Give You Pra Pra Medley There is Se In Nonye Mo ji i rẹ̀ lónìí Apata ayeraye ayeraye Ọlọrun ayeraye ayeraye agbára mi kò mọ pé ẹ pè é lè ṣe é Àta Èdìdì.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Níyì Akínmọlá jẹ́ olùgbéré-jáde, adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile ati adari ile-iṣẹ AntHill Productions, ti won ti n gbe ere ọlọkàn-o-jokan jade.ibẹrẹ aye reakìnÀṣà je Yoruba ọmọ bibi Ipinle Ondo ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ní ilé-ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Yaba College of Technology,Iṣẹ́ reakìntì kọ́kọ́ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ olùṣètò àwòrán, Alágún Webutò àti Ọmọlẹ́yìn olùgbéré-jáde kan ní ilé-iṣẹ́ Nollywood, láwọn àsìkò yí, ó bẹ̀rẹ̀ sí mọ̀ nípa nítẹ ní ṣíwá káwò, Animẹsan After effect and vište Effect effect ọ̀gá rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Eré tí ó sọọ́ di ìlú-mọ̀ọ́ká ni Kájọlà tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2010 ni ó jẹ́ àyẹ̀wò nípa ìlò ìlò Visual edféct láti fi gbé eré jáde, Àmọ́ wọ́n gbẹ́sẹ̀ lé eré yí látàrí wípé eré yí lùgbàdì ìlàn òfin ìgbérẹ̀ jáde .. | wikipedia | yo |
Ó tún darí eré out of luck ti Linda Ọkànsty, Tope Nop àti Jide Kosoko kópa nínú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ere yi ni o je ki won yan Akinmọ fun ami-eye ti adari ere to peregede julo nibi ayeye ami-eye ti 2016 Nigeria Entertainment Award.Níyì gbe ere kan ti o pe ni Plaything ere ti o je ni odun 2016.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣàfihàn eré yi ní Gbogàn FilmOne Ixx Cinéma ní Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó di ọdún 2017, ó tún gbé eré kan kádé tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní The Arbitration, àwọn òṣèré Jandaran-Janted bíi O.C Noumair ni wọ́n kópa , tí wọ́n sì fara hàn nínu ayẹyẹ àpèjẹ ọdún eré oníṣe tí ó wáyé ní ìlú Toronto.Ìwúrí àṣeyọrí rẹ̀ lórí eré The Arbitration ni ó mú u gbé eré míràn jáde pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́ fries-camjá WaBMco wá Plc, ni ó fi gbé eré "Adventures of lọ́lá and ChuChuts" jáde ní ọdún 2017.Àwọn àṣàyàn eré Wọ̀mọ̀ ènìyàn Alààyè Film Directors Ọjọ́ìbí ní 1982 Film Film College of Technology Ọdún Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
ỌLÁDÉDÉ OLOOGUN TÍ A tún mọ̀ OANRAN ỌMỌ OLO Emmanuel TÍ WỌ́N bí lọ́jọ́ Ke-an Oṣù Kẹfà Ọdún 1986,( 9, 1986) jẹ́ òṣèrébìnrin, afẹ̀̀kan-sojú àti atọ́kùn ètò ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O ti fìgbà kan jẹ́ Aji-sójú ọ̀sẹ̀ luxìgbésí-ayé rẹwọn bí Ọláí ỌláOgun ní Ìlú Èkó lọ́jọ́ Késàn-án osù kẹfà ọdún 1986.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè nínú èdè òyìnbó ní University of Lagos.Ó di gbajúmọ̀ òṣèré ní Nàìjíríà àti Ghana nígbà tí ó kópa nínú eré kan tí Wale Adénúa gbé jáde lórí tẹlifísàn, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "soul Sisters and She was also in the Yoruba series gb Story.Lọ́dún 2007, ó gba ipò Genevieve Nnaji gẹ́gẹ́ bí Agé-sójú nínú ìpolówó-Ọjà ọ̀sẹ̀ lux And continued in This Role until 2009.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ afọ̀gé-sójú ilé iṣẹ́ aṣerunlóge, Diva Hair Extension, Fuman juice àti ilé-ìfowópamọ́ United Bank for Africa (UBA).Ìgbésí-ayé ara Adéfunmi fẹ́ Babátúndé ojora Emmanuel lóko lọ́dún 2015 Wọ́n sìn bímọ kan péré fún ara wọn lọ́dún 2016.. | wikipedia | yo |
She was married to Babatunde ojora in 2019.Àtẹ aṣayan àwọn iṣẹ́ rẹàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Olabisi Aabebi ti won bi lọjọ kokanlelogbon osu Kẹwàá odun 1975 (31 October 1975) je gbajumo elere idaraya sise-ehoro nigba kan ri, ti o je omo bibi ilu Ilorin ni ipinle Kwara.. | wikipedia | yo |
O wa lara iko egbe elere ti won gba amin-eye baba ni idije Olimpiiki Lọ́dún 1996 ninu idije ere gbagigbagi onídu 4 400 400.O gbamin awon oje wẹ́wẹ́ ninu ere sísá ipinle 1994 ati amin ati elere fun elere ile Adulawo lo 1995.. | wikipedia | yo |
O ti bímọ báyìí lẹ́yìn tó lọ́kọ.Àtẹ Aṣayan àwọn àṣeyọrí ìdíje rẹàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Abimbola Adefẹ́Abimbola Àdùnní Adéfẹ́gbè ( ọjọ́ ibi 15 September[ọdún? Ó jẹ́ òǹkọ̀wé Nàìjíríà.Ìgbésí ayéa bíi ní ìlú Ìbàdàn, Southwest Nàìjíríà, ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Ìbàdàn, níbití ó ti jáde pẹ̀lú Bachelor's degree àti Master of Arts degree in communication and language arts.Ó jáde pẹ̀lú Ph.D.. | wikipedia | yo |
Nínú ìko and eré orí ìtàgé ní University of Texas, Austin.[1]Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú The Punch Newspaper ní ìlú Èkó, Nàìjíríà, gẹ́gẹ́bí ònkọ̀wé.. | wikipedia | yo |
O sise pelu The Punch Newspaper ni, Naijiria, gegebi onkowe.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ nipa Modern African Culture bi wọn ṣe n gbe ati ṣiṣe Through the Disciplinary Lenses of performance, Gender, Africana, and Yoruba Studies.. | wikipedia | yo |
O kọ oriṣiriṣi iwe ẹkọ ti wọ́n ti tẹ̀ jade ní oriṣiriṣi journals pẹlu Journal of Women and Religion, and Journal of Culture and African Women Studies.. | wikipedia | yo |
Retrieved 2009-11-21.External linkSunder the brown Tẹ́du Roofs - Review in Saraba Magazine[permanent dead link] Writers' Tour starts on a good note - Guardian[dead link]This article about a Nigerian writer or poet is a stub.. | wikipedia | yo |
Ejiro Amos Tafírí jẹ́ gbajúmọ̀ Asoṣọ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ti o da silẹ lati maa ránso igbalode awọn obinrin.igbesi aye ati iṣe rẹ lati ibẹrẹEjiro jẹ ọmọ bibi Ipinle Delta, ṣugbọn ti wọn bi si ipinlẹ Eko.. | wikipedia | yo |
Láti kékeré lọ́mọdún mẹ́ta ló ti nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ aránṣọ nípasẹ̀ ìyá rẹ̀ àgbà tí wọ́n jẹ́ aránṣọ .. | wikipedia | yo |
Awon obi re fe ki kawe gboye Dokita oyinbo, sugbon kaka bee o lo kawe gboye ninu imo aṣọ ati aṣọ rírán ni Yaba College of Technology.Ọdun 2010 ni Ejiro da ẹya ìránṣo tire silẹ ti o pe ni e.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2015, ẹ̀yà ìránṣo rẹ̀ é.A.T, tí wọ́n tún sọ ní "The Madame", ṣe àfihàn níbi Ìpàtẹ Agbobíà ìgbàlódé tí wọ́n ṣe ní ọ̀sẹ̀ Ìpàtẹ Agbobíà ìgbàlódé ní Port Harcourt àti Kenya.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |