cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó kúrò ní ìlú Nàìjíríà ní ọdún 2001 lọ sí Amẹ́ríkà níbití ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìṣàkóso ìṣòwò ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga District of Columbia, Washington, DC.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀síwájú láti kọ́ ẹ̀kọ́ orin fún àléfà óyè rẹ̀ ní Ilé-ẹkọ́ gíga Kátólíkì, Washington.. | wikipedia | yo |
CPD Nígbàtí ó n kọrin fún díẹ̀ nínú àwọn ólùdarí gbajúgbajà àgbáyé ní òde òní, a ti ṣe àpèjúwe rẹ̀ bi ọ̀kan nínú àwọn ohun tí ó dára jùlọ ní àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Ó ti kọrin káàkiri àgbáyé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ólùdarí àgbáyé pẹ̀lú àwọn àarẹ àti Ọba, àwọn Ikọ̀, àti àwọn ọmọ ile-igbimọ ijọba.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009 ó ṣe àgbéjáde Akjọpọ tí àwọn ewi ìfẹ́ rẹ̀ tí a pè ní "Ìṣesí Ọmọ Ọba-bìnrin". jẹ́ olórí Àjọ Àjọ̀, ó sí maa máa ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìtọ́ni.. | wikipedia | yo |
Àjọ ẹ̀bùn rẹ̀ n pèse àwọn sikolashipu fún àwọn ọmọbìrin ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkawọ́n ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Gloria Olusola bámiloyè tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin Oṣù Kejì Ọdún 1964 jẹ́ gbajúmọ̀ olùdarí, olóòtú òṣèrébìnri sinimá àgbéléwò, àti oníTiata ọmọ bíbí ìlú Ileṣa ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
She is à co-úntá of Mount Zion drama Ministry.Ìgbésí ayé rẹ̀ ni ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Gloria sí ìlú Iléṣà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 1964.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ láti di olùkọ́ ní DiVisional Teachers Training College ní ìlú Ipetumodu.Òun àti ọkọ rẹ̀, Mike bámiloyè ni wọ́n jọ dá ilé isẹ́ Sínì a àgbéléwò Mount Zion Faith Ministry sílẹ̀ lọ́jọ́ karùn-ún oṣù Kẹjọ Ọdún 1985.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa, tí ó sin ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò àti eré orí ìtàgé lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
LỌ́DÚN 2002, ó kọ ìwé kan tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní "The Anxiety of single Sisters "Àtòjọ àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀The háúnting Shadows 1 (2005)The háúnting Shadows 2 (2005)The háúnting Shadows 3 ( 2005) calling 1, 2 & 3 (2020 (2020 & 2 (2020)My Mother In Law 1, 2 & 3 (2020)Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Juliana iṣtobilọba Oloyede, tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ n jẹ́ Toyo Baby, nípa ipa tí ó kó nínú eré Jenifa's Diary gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà-ìtàn, Towa jẹ́ oserebìnri sinimá àgbéléwò àti ti Fefí, ó tún jẹ́ àṣegbé fún ìbálòpọ̀-ètò ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká nípa àtakò rẹ̀ sí ìbálòpọ̀ lọ́kọláya láìṣe ìgbéyàwó tó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọ̀dọ́.Ìgbésí-ayé rẹ̀ ni ìbẹ̀rẹ̀ a bí Juliana sí ìlú Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Yakubu Mohammed tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n Oṣù Kẹta Ọdún 1973 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, adarí eré, olórin àti olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ aṣoju ati olùpolówó ọja fun ile-iṣẹ ibara sọrọ ti Globacom.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ aṣoju fun ajo SDC , o si tun fìgbà kan jẹ aṣoju fun ile-iṣẹ Ambassador and Nescafé becasal.. | wikipedia | yo |
Yakubu Mohammed jẹ́ ọ̀kan lára àwọn lààmì-laaka ní Kannywood àti Nollywood.. | wikipedia | yo |
ó ti kọ orin tí ó ti lé ní ẹgbẹ̀rún ún, ó ti kópa nínú eré rí ó ti tó ọgọ̣́rún un nínú eré Hausa.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó yá, ó kẹ́kọ̀ọ́ síwájú sí nínú iṣẹ́ tíátà, tí ó sì gòkè àgbà nínú iṣẹ́ tí ó yàn ìyò.. | wikipedia | yo |
Yakubu tún jẹ́ olórin tí ó sì ti gbé orin tí ó tó ẹgbẹ̀rún kan jáde fún àwọn eré sinimá àgbéléwò lọ́kan ò jọ̀kan àti àwọn mìíràn ní èdè Hausa àti Gẹ̀ẹ́sì, Òun àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ n ṣiṣẹ́ pọ̀ Sani Musa Danja.. | wikipedia | yo |
Sharon Oòja tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà Oṣù Kẹrin Ọdún 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́yìn tó kópa nínu eré kan tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní Skinny Girl in Transit, nínu èyí tí ó kópa ẹ̀dà-ìtàn Salewa .ÌGBÉSÍ-ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀Sharon jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Benue, ṣùgbọ́n tí wọ́n bí sí Ìpínlẹ̀ Kaduna, tí wọ́n sin tó dàgbà ní Ìpínlẹ̀ Plateau lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré nígbà tí ó dèrò ẹ̀kọ́ lọ́dún 2013.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé alágbàwẹ̀ ẹ̀yì nínú iṣẹ́ ìròyìn ní Yunifásítì houʹtos North American University Benin.. | wikipedia | yo |
Oun ati Timini Egbuson ti fìgbà kan se olóòtú fún ètò ọ̀sẹ̀ Oge ti ilé ìfowópamọ́, GTBank ṣe agbátẹrù rẹ̀ lọ́dún in 2017.Àtòjọ àṣàyàn àwọn sinimá àgbéléwò Recoming from InSanity (2020) Oloture (2019) King of Boys (2018) Skinny Girl In Transit (2016-) lára and The Beat Coming From InSanity Moms at War From Lagos With Love (2018) The Men's Club Paper Lagosians (2019) The Bos Bons Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
AWAAT SOEDI JẸ́ GBAJÚMỌ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàn án fún Àmín ẹ̀yẹ ti òṣèrébìnrin tó dára jù ní ipò Olú-ẹ̀dá-Ìtàn, Africa Movie Academy Award for Best Actress in a leading Role lọ́dún 2011 fún ipa tí ó kó nínu sinimá àgbéléwò, Aramotu.Iṣẹ́ rẹ̀ Ìdíat jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
In 2011, Idiat Revealed To Vanguard, That Her Role in Aramotu as a Woman of Afòté, Progboted Her to Champion a case for Gender Equality in Nigeria.. | wikipedia | yo |
Ìdí tí kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, lára wọn ni; ìyàwó Saaraa, Àbọ̀dé Mecca, Kóńdó́à ọlọ́pàá, ọmọ ìyá Àjọ Ti Aramotu | wikipedia | yo |
Other Notable Films Includes, Kóńdóta ọlọ́ (2007), Lágo Ọjọ́ (2008) And Ìgbẹ̀yìn Ìtànd (2009).Lọ́dún 2010, Ìdí kópa Olú ẹdá Ìtàn Nínú Sinimá Aramotu | wikipedia | yo |
Sinimá tó sọ nípa ipa pàtàkì ti àwọn obìnrin Yorùbá láwùjọ.. | wikipedia | yo |
Ipa yìí mú kí wọ́n yàn án fún Àmín-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù ní ipò Olú-Ẹ̀ko-Ìtàn, Africa Movie Academy Award for Best Actress in a leading Role, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò gbà á.. | wikipedia | yo |
O padanu ami eye fun akẹgbẹ́ rẹ, ama Abẹ́brese Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Adélà Juyitan jẹ́ oníṣòwò àwùjọ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Alákóso ti Glitz Group of Companies Àti Ààrẹ fún Junior Chamber International ní ọdún 2019.Ìgbésí ayé Juyitan jé ọmọ Ìpínlẹ̀ Òndó ṣùgbọ́n a bíi ní ìlú Èkó, ó jẹ́ àkọ́bí nínú àwọn ọmọ márun.. | wikipedia | yo |
O keko gboye ninu eko iṣiro lati ile-eko giga ti ipinle Ekiti, o si gba oye oluwa ti isakoso isowo lati ile-eko giga Lincoln, California, ni ilu Amerika.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2004, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé ìfowópamọ́ Zenith gẹ́gẹ́ bíi Agùnbánirọ̀, ó sin gba ìgaga ipò títí di Oṣù kẹ̀sán ọdún 2013 nígbàtí ó darapọ̀ mọ́ ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ fún Áfíríkà (United Bank for Africa) gẹ́gẹ́ bíi olùṣàkóso ìṣòwò, Lẹhinna lọ kúrò ní ọdún 2015 láti ṣètò ilé-iṣẹ́ tirẹ̀ tí a pè ní Glitz Occasions Nigeria Limited .. | wikipedia | yo |
a yàn n gẹ́gẹ́ bíi Alákoso Junior Chamber International ti orílẹ̀-èdè Nàijíríà ní ọdún 2019.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ará Nàìíawọn ẹ̀nìyàn alààyẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lọ́lá Margaret tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ lọ́lá Margaret Oladipupo jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa Olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Bísola Aláàánú.Igba Ewe àti ìkẹ́kọ̀ọ́wọ́n bí Lọlá ní Iléṣà, ni a city located in Ìpínlẹ̀ Osun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O kawe gbàwẹ̀ ẹ̀ri digírì ninu imọ ẹkọ itan ati ibaṣepọ Orilẹ-ede si Orilẹ-ede, (History and International Relations) ni Yunifasiti Ipinle Eko, Lagos State University.Iṣẹ rẹlola Margaret bẹrẹ iṣẹ Tiata pẹlu ìràlọ́wọ́ Bọlaji Amúṣan, gbajumọ oṣere alawada ọmọ Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa Olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ bisola Aláàánú.. | wikipedia | yo |
Lọlá ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá mìíràn bíi ẹyin àkùkọ àti ọmọ ọlọ́rọ̀, èyí tí òun náà ṣe olóòtú rẹ̀ tí àwọn àgbà òṣèré bíi Faithia Balógun àti Mercy aigbé kópa nínú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó ti kópa nínú oríṣiríṣi sinimá àgbéléwò.Àtòjọ àṣàyàn àwọn Sínì a àgbéléwò rẹ̀ bisoko Aláàánú Ẹyin àkùkọ, 2008 ọmọ ọlọ́rọ̀, 2016 AGBÁRA ÌFẸ́ (The Power of Love), 2016Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Nuella ńjubigbọ́ jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, ònkọ̀tàn sinimá àgbéléwò, arẹwà àti olóòtú tẹlifíṣàn ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sìn yàn án fún ìdíje àmìn ẹ̀yẹ 2012 Nollywood Movies Awardsfún òṣèré tó ń dàgbà jù lọ lọ́dún 2012 .Igba Ewe àti ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí Nuella Namiïgbo lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1984 ní ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ètò ìṣèjọba àti àkóso àwùjọ, (Government and Public Administration) ní ìmọ̀ State University.. | wikipedia | yo |
O sin orile ede baba re ni Ipinle Delta fun akanṣe isinlu, National Youth Service Corps.igbesi aye rẹ lọjọ kokandinlogbon osu keta odun 2014, oun ati gbajumọ oludari sinima agbelewo, tchidi Chikere fe ara won.. | wikipedia | yo |
Awuyewuye pọ̀ lórí igbeyawo wọn nítorí pé ọkọ rẹ ti kọ́kọ́ fẹ́ iyawo kan tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó fẹ́ ara wọn.. | wikipedia | yo |
Sophia Chikere, tí òun náà jẹ́ òṣèrébìnrin ní ọkọ rẹ̀ kọ́kọ́ fẹ́, tí wọ́n sin ti bímọ fún ara wọn.. | wikipedia | yo |
tchìdí, ọkọ rẹ kò ṣàiṣàlàyé ìdí tí igbeyawo akọkọ fi forí sanpan lẹ́yìn ọpọlọpọ awuyewuye wọnyi.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bímọ kan fún ara wọn lẹ́yìn igbeyawo naa.O dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1999, eré àkọ́kọ́ tó s̩e ní "Royal Destiny" | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà, ó ti kópa nínú sinimá tí ó ti ju àádọ́rùnún lọ.. | wikipedia | yo |
O ti ba awọn gbajumọ oṣere bi i Ini Edo, Mercy Johnson, Desmond Elliot, Uche Jombo, Genevieve Nnaji, John Okafor, pẹ̀tẹ̀ Edochie ati Ken Eric's ṣere po.. | wikipedia | yo |
.Àtòjọ àwọn àṣàyàn sinimá relife's Inkápáẹsẹ̀rd of Marriage Evil Project heart of a Slaveroalet grandmother Open & Close (2011) Luta WBOPlace Omin Eye Africa Magic Viewers Choice Awards City People Entertainment Awards Rising Star Award 2012.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Timini Egbuson tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 1987, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde àti Olúpa lórí ẹ̀rọ ayélujára.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọ́n bí Timini ní ìpínlẹ̀ Bàta, ó jẹ́ àbúrò fún gbajú-gbajà òṣèré Dakore Egbuson Akande.. | wikipedia | yo |
O lọ si ile-eko alakoobere ti Greenspring Montessori, the Afro School and St Catherine's.. | wikipedia | yo |
Ó tún l9 sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Adebayo Mokúolu College ní Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Psychology ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé ṣíṣe ní ọdún 2010 nígbà Rtí ó kópa nínu eré onípele níàmì-dègbà ti Tinsel.. | wikipedia | yo |
Timini gba ami-eye ti AMVCA Awards fun òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ 0aa paa jùlọ fún ipa tí ó kó nínú eré Elevator Baby.Àwọn àṣàyàn eré retimini ti kópa nínu àwọn eré tí ó ti pọ̀ "MTV Shuga""Fifty”“Skinny Girl in Transit""manmohunting with Mum""TinselFifty the series""isoken""wsomething Spheanother Time""Room 420""timested the Missing piece Intern""Eleator Baby""s Girl Conve Code"Awards and Nomas Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Ey ní 1987-21st Century Nigerian Mamba Actors lá Gboki Actors From GG State of Lagos Aluru.. | wikipedia | yo |
Bose Ogulu je omowe, onisowo obinrin ati aláàkóso omo orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ogulu ni Rebeka Burna Boy's eyi ti i se ise orin kiko omo re, idi ni yi ti won tun fi mo o si Mama Burnaibere aye re Ogulu je omo bibi inu benson Idonije, eniti n se ilu mo o ka olorin omo orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Pẹ̀lú oyè alákokokò ti Yunifásítì (Bachelor of Art degree) tí ó gbà nínú ìmọ̀ lórí i àwọn èdè àjèjì àti oyè onípele kejì (Masters of Art degree) tí ó gbà nínú ìmọ̀ lórí i ìtunmọ̀ èdè láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ìlú Port Harcourt.. | wikipedia | yo |
Ogulu se aseyori ninu ise re gege bi i olutunmo ede fun awon ile-isowo ti iwo-oorun Afirika (Federation of West Africa Chambers of Commerce).. | wikipedia | yo |
Awon ede bi i ede Geesi, Faranse, Jemani, Italia ati ede Yoruba ja geere ni enu re.. | wikipedia | yo |
Idi ni yi ti o fi da ile-iwe ti won ti n ko ede , ti won n pe ni awon Afara Ede (language Bridges), sile.. | wikipedia | yo |
Ile-eko yi ni o ti se eto irin-ajo ti asa fun awon oódo ti o le ni egbesan an (1,800).Ni afikun, Ogulu sise gege bi i oluko ede Faranse fun opolopo odun ni Yunifasiti ti imo eko ti o wa ni ilu Port Harcourt.. | wikipedia | yo |
Ó fi ẹ̀yìn tí ní ẹnu iṣẹ́ ní ọdún 2018.Iṣẹ́ rẹ̀ Ogulu n se aláàkóso awon ise orin Dmini omo re, eni ti o n sise orin labe oruko Burna Boy eyi ti opo eniyan mo o si.. | wikipedia | yo |
O tun n ṣe akoso iṣe orin Nissi omo re obinrin, eni ti o n sise orin labẹ Nissi ti i se orukọ rẹ gangan.. | wikipedia | yo |
Ogulu se Rebeka fun Burna Boy titi di odun 2014 ki o to tun wa di Rebeka omo re yi pada lati odun 2017 siwaju.. | wikipedia | yo |
Èyí ni ó fún un ní orúkọ inagijẹ, Mama Burna ti ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ ó sí.. | wikipedia | yo |
Ogulu ti gba awon ami eye fun Burna Boy omo re nibi opo ayeye ti o ti se asoju re.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn àmì ẹ̀yẹ yí ní àwọn ẹ̀bùn orin ti Áfíríkà (All Africa Music Awards), The Headdies àti MTV Europe Music Award.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó gbọ́ wípé ọmọ rẹ̀, Burna Boy ti borí láti gba àmì ẹ̀yẹ ọdún 2019 ti MTV fún òṣèré Áfíríkà tí ó dára jùlọ, lesekese ni ó pè é níbi tí ó ti ń ṣe eré lọ́wọ́ láti lè sọ ìròyìn ayò yí fún un.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí Burna Boy gba àwọn ẹ̀bùn mẹ́rin kan níbi ayẹyẹ àwọn àmì ẹ̀yẹ ti Soundcity MVP ti ọdún 2018, Ogulu ni ó lo se asoju fún ọmọ rẹ̀ níbi yí ni ó ti sọ ọ̀rọ̀ tí ó fa ìdùn àwọn akọìròyìn nígbà tí ó sọ pé " Ẹ Mã a reti isinwin díẹ̀ sí." Ni ibi awon ami eye ti Bet tí wọ́n ṣe ní ọdún 2019 ní ìlú California, Ogulu lo lo se asoju omo re láti gba àmì eye fún un fún Best Internation Act.. | wikipedia | yo |
Nibi ami eye yi ni o ti ka a ninu oro re nibiti o ti n sọ fun awon omo ile Afirika ti o ti di omo orile-ede Amerika pe ki won ranti wipe omo ile Afirika ni won ki o to di wipe won di ohunkohun.. | wikipedia | yo |
Oro re yi mu ki opo eniyan dideduro pàtẹ́wọ́.Bose Ogulu ni alase ati oludasile ti Spaceship Collective ati Spaceship Publishing (Aṣọ atẹjade).Ìgbésí aye re Bose Ogulu se igbeyawo pelu Samuel Ogulu ni ogbon odun seyin ti won si bi omo meta ti oruko won n je Dmini, Oluroko ati Nissi Ogulu.Awon ìtọ́kasí awon eniyan alààyè.. | wikipedia | yo |
Enilọba Ajayi jẹ́ agbẹjọ́rò, ajàfẹ́tọ̀ọ́ abarapá ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O gba amin ẹyẹ Mandela Washington Fellowship lodun 2016.. | wikipedia | yo |
O kawe gbawẹ ẹri dìgírì keji ninu imọ ofin, International Law lati University of Helforfor, ni orilẹ-ede United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Lara akitiyan rẹ fun eto awon abarapa iran 2020 Naijiria fun awon abarapa (Nigeria Vision 2020 on disabilities) ati ofin Ipinle Eko lori awon abarapa.. | wikipedia | yo |
O ti ko iwe mẹta.Igba ewe ati Ìkẹ́kọ̀ọ́ RẹAjayi jẹ ọkan lara àwọn ọmọ marun-un ti àwọn obi rẹ bi.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ lọ́ra láti fi í sí ilé-ìwé nígbà èwe rẹ̀ nítorí pé ó jẹ́ alábaràte.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́ta, ó sìn parí ẹ̀kọ́.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ de Yunifasiti ninu imo ofin ki o to dèrò oke-okun lati Tetsiwaju lati kawe gbàwé eri digírì keji, (Masters degree) ni University of Helforfor.Àwọn akitiyan yan iṣe rẹni olodun aye rẹ, o sise ni mobility aid and appliances research and development center.. | wikipedia | yo |
O kopa ninu eto iran ọdun 2020 fun awọn ṣakoso (Nigeria Vision 2020 on disabilities Matters), bẹẹ lo wa lara awọn ti won kọwe ofin eto awọn ṣakoso ni Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
She was awarded a Mandela Washington Fellowship in 2016... | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2017, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ as of January 2017 Benola cerebral palsy inititheun.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àkóso Àjọ “Let CP Kids Learn", èyí ÀJỌ tó n ṣe ìrànlọ́wọ́ àti Ìdàgbàsókè àwọn ọmọ olùṣẹ̀sókè .àwọn ní HanRI Ìtọ́kasíLIST} {.. | wikipedia | yo |
Uche Jombo Rodriguez tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1979 (December 28, 1979), jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti ònkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà.ÌGBÉSÍ ayé rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ bí Uche Jombo sí ìlú Abirìbá, ní Ìpínlẹ̀ Ábíá, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1979.. | wikipedia | yo |
Dorcas Sola FDPson jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tó kó nínu ètò kan tí wọ́n pè ní ṣúgà lóri ìkànnì MTV's.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2020, ó padà sí ètò ṣúgà náà lórí ìkànnì MTV láti sọ̀rọ̀ lórí àjàkálẹ̀ àrùn korona pẹ̀lú àwọn òṣèré tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pọ̀ káàkiri ilẹ̀ adúláwọ̀ Áfíríkàìgbésí ayé rẹ̀wọ́n bí Fápson nílúi London ní nǹkan bí ọdún Ṣíṣe… | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ iṣẹ́ ọ̀daràn (Criology) LÓRÍLẸ̀ èdè England.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó sin kàwé gboyè nínú ìmọ̀ tíátà ní New York.Ó kópa nínú ètò ṣúgà Abala Kẹta ní ìkànnì MTV.. | wikipedia | yo |
As ‘Sophie’ and she was the presenter of "the juice" an Interview series for KandaniTV.O wa ninu ètò ṣúgà ní ikanni MTV ti o o tun fi pada di akosemose iṣẹgun ti won pe ni "Sophie" ninu ètò mìíràn ti won pe ni MTV Shuga Alone Together nibi ti won ti n soro nipa ajakale arun korona lodun 2020.. | wikipedia | yo |
The series was written by Túndé àlàdẹ̀ṣẹ and Broadcast for several Nights - its backers include the United Nations.. | wikipedia | yo |
Felicial Adetoun Omolara Ogunseye ( ti o je ọmọbíbí inu Banjo) ni a bi ni ojo karun un osu kejila odun 1926.. | wikipedia | yo |
Adetoun ni ojogbon obinrin akoko ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ìjìnlẹ̀ lórí ilé ìkọ̀wé pamọ́ sí ka (Library and Information Science) ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Yunifásítì ìlú Ìbàdàn.Ìbẹ̀rẹ̀ àyè rẹ̀ àti Èkó a bí Ogunseye ní ọjọ́ karùn ún oṣù Kejìlá ọdún 1926 ní ìlú Benin, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O je egbon agba fun ogagun Victor Banjo ati Ademola Banjo.. | wikipedia | yo |