cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ní ọdún 2014, ipa tí ó kó nínú eré Lagos Cougars àti Perfect Union tí ó sì ti mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèré tó ní ọjọ́ ọ̀la.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ yí kàn náà ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013, o ko ipa "Joke" ninu ere Lagos Cougars, ipa kan ti o fun lánfàní yiyan fun ti oṣere ti o dara julọ ni ipa asiwaju nibi ikede ẹlẹlara ti African Movie Academy Awards ati Nigeria Entertainment Awards ti ọdun 2014.Ìgbé ayé rẹ Okeke ni a bi ni Oṣu kèéta ọjọ 26, ọdun 1987.. | wikipedia | yo |
Okeke jẹ ẹnikan ti o fẹran awọn ọkọ bọgini.Aṣa ere rẹ ligak Ladies (2007) Stronger than Pain (2007) Lagos CougarṢáwọn Ìtọ́kasí awọn eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
Stephanie Linus (Stephanie Onyekachi Okereke; 2 Oṣù Kẹẹ̀wá 1982) jẹ oṣere, oludari ere ati afẹwaṣiṣẹ.. | wikipedia | yo |
O ti gba ọpọlọpọ awọn ami-eye ati awọn yiyan fun iṣẹ rẹ bi oṣere, to fi mọ ami-ẹyẹ ti Reel ti ọdun 2003 fun oṣere ti o dara julọ, ami-ẹyẹ Afro Hollywood ti ọdun 2006 fun oṣere ti o dara julọ, ati awọn yiyan mẹta miran fun oṣere ti o dara julọ ni ipa asiwaju nibi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards ni ọdun 2005, 2009 ati 2010.O tun jẹ oludije nibi idije ẹwa ti Naijiria ni ọdun 2002.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2011, ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dá lọ́lá pẹ̀lú fífún ní oyè Memeber of the order of the Federal Republic (MFR).Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ Stephanie Okereke ni a bi ní NGOR Okpala, ní ìpínlẹ̀ Imo .. | wikipedia | yo |
Ó parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìpínlẹ̀ Delta.. | wikipedia | yo |
O keeko giga ni Yunifasiti ilu Calabar, ni Ipinle Cross River, nibi ti o ti gba oye-ẹkọ ninu imo ede Gẹẹsi.Iṣẹ Iṣẹ ni akoko igba ti o si wa ni ọdọ ni ọdun 1997, o han ninu awọn fiimu Nollywood meji kan; Compromi 2 ati Waterloo.. | wikipedia | yo |
Nibi idije ẹwa Naijiria ti ọdun 2002 ti o ti kopa, Okereke se ipo keji.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2003, Okereke gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ méjì, nínú mẹ́jọ tí wọ́n yàán fún, níbi ayẹyẹ Reel Awards ti ọdún 2003 fún òṣèré tí ó dára jùlọ.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ipari ẹkọ lati Ile-ẹkọ giga New York Film Academy ni ọdun 2007, Okereke ṣe agbejade fiimu ti akọle rẹ jẹ Through the Glass eyiti o ṣe pe oun ni o ṣeto kikọ ati didari ere naa, ti o si tun kopa ninu rẹ.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà rí yíyan Africa Movie Academy fún àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó ṣe àgbéjáde fíìmù míràn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ dry.. | wikipedia | yo |
Oun yìí kan naa lọ́tùn ṣeto kikọ ati didari, bẹẹ lo si tun kopa ninu ere naa, eyi ti o gba ọpọlọpọ awọn ami-ẹyẹ to fi mọ ti Africa Movie Awards ẹlẹkejila ati ti Africa Magic Viewers Choice Awards ti ọdun 2016 fun fiimu ti o dara julọ pẹlu ẹbun ọkọ ayọkẹlẹ tuntun kan.. | wikipedia | yo |
Okereke ti kopa ninu fiimu to le ni aadọrun-un.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1982.. | wikipedia | yo |
Thelma Okoduwa Ojiji (ti a bi ni Oṣu kèéta ọjọ Kẹẹ̀sán) jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
O ri yiyan gẹgẹbi amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ oṣere ti o dara julọ ni ọdun 2012 nibi ayẹyẹ Africa Movie Academy Award.Iṣẹ iṣe rẹ ninu ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Iwe irohin Encomium, Thelma fi han pe oun wa si idi-iṣẹ fiimu nipasẹ Chico Ejiro.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ó ṣiṣẹ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́ Norbert Young nínú fíìmù Aggregator.. | wikipedia | yo |
Ó ti ṣe ìfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tẹlifíṣọ̀nù tó fi mọ́ Tinsel, Beautiful Liars, Treasures, Spider àti Family ties.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó kó ipa “Linda” nínú eré ìfẹ́ kan, Mr and Mrs.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti o ṣe igbeyawo, o sọ di mimọ wipe nigbagbogbo ni ọkọ oun maa n ṣe agbeyẹwo awọn ipa ti oun ni lati ṣe ninu fiimu, bi ko ba si ti fọwọsi, oun yoo ko ṣiṣẹ iru ipa bẹẹ.. | wikipedia | yo |
Ninu ifọrọwanilẹnuwo pẹlu The Punch, o tọka si Joke Silva ati Richard Mofe-Damijo gẹgẹ bi awọn ti wọn maa n fun oun ni iwuri ni Nollywood.. | wikipedia | yo |
O tun tọka si ipa rẹ bi "arinọla Cardoso" ninu ere Hush ti Africa Magic kan lati je ipa ipenija julọ ninu ise fihanna aye rẹ ara ilu Uromimi ni Thelma ni Ipinle Edo.. | wikipedia | yo |
O keeko imo-ijinle komputa lati ile-eko giga Yunifasiti ilu Port Harcourt.. | wikipedia | yo |
Ó tún gba oyè-ẹ̀kọ́ ní eré ìtàgé láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan náà.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 2009, ó ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Onya Otì.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Nnenna Rachael Okonkwo (ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon, Oṣu Kaàrún ọdun 1987) ti a mọ si Nkoli Nwa Nsukka jẹ oṣere fiimu ọmọ orilẹ-ede Naijiria .. | wikipedia | yo |
O gbajumọ julọ fun fiimu Nkoli Nwa Nsukka.Igbe aye ati iṣẹ rẹ Rachael Okonkwo wa lati UKpata ni agbegbe Uzo Uent ti Ipinle Enugu.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ ere ṣiṣe ni akoko igba ti o wa lọmọdé, ṣugbọn nitori aini awọn ipa fiimu o yipada si iṣẹ ijo.. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ Nollywood ni ọdun 2007 lẹni to n ṣe awọn ipa kékèèké.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2008, ó ṣe ipa amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fún Ini Ẹdó àti Van Vicker nínu eré Royal War 2.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010 bákan náà, o pẹlu Patience Ozokwor ati John Okafor jọ ṣe apa kinni ati apa keji ere Open and Close.. | wikipedia | yo |
Ipa akọkọ rẹ to ṣe gboogi waye ni ọdun 2014, nibi ti o ti ko ipa asiwaju ninu ere Nkoli Nwa Nsukka gẹgẹ bi Nkoli.. | wikipedia | yo |
Iya rẹ ku ni ọdun 2020.Awọn iṣe Iferan Omoni rẹayẹyẹ Ọjọ Aji'nde fun Awọn ọmọde Rachael Okonkwo maa n ṣe agbatẹru ayẹyẹ lọdọọdun, pẹlu alapọ lati pese awọn ẹbun ọfẹ fun awọn ọmọde ati lati da awọn eniyan lara ya.. | wikipedia | yo |
Ó sọ pé ètò náà maa ń jẹ́ kí òun ní ìṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn tí wọ́n fẹ́ oun.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2015, Rachael ṣe agbatẹru ẹda akọkọ ti ayẹyẹ ọjọ Aji'nde fun awọn ọmọde pẹlu ikun lati pese awọn ẹbun ọfẹ fun awọn ọmọ wẹ́wẹ́ ni akoko ayẹyẹ ọjọ Aji'nde ni Enugu.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016 ẹ̀dà ẹ̀kejì tí ó wáyé ní Onitsha ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò ju ti àtẹ̀yìnwá lọ pẹ̀lú wíwá àwọn òṣèré akẹgbẹ́ rẹ̀ bi Ken Erics àti àwọn míràn.. | wikipedia | yo |
Ẹda ti 2017, eyiti o waye ni ilu bibi rẹ,Nsukka, ni akojọpọ awọn eniyan to le ni 5000.. | wikipedia | yo |
Lára wọn ni àwọn gbajugbaja bí Angela Okorie, Nonso Diobi, slowdog, Ken Erics, Nani Bobo, Eve Esin ati àwọn miran.. | wikipedia | yo |
O tun ri atilẹyin awọn ile-itaja nla, eyi to mu ki ẹda ti ọdun naa tobi ju awọn to ti ṣaaju rẹ lọ.Awon itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1987awon eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún ti amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu àwọn fíìmù tó lé ní ojú-ún.ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Okorie jẹ́ èkéeta nínu àwọn ọmọ márùn-ún ti òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
A bi ni ilu Cotonou, orile-ede Benin Republic nibi ti o si dagba si.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tí ó ti kẹ́ẹ̀kọ́ ìṣàkóso ìlú .. | wikipedia | yo |
O jẹ ara ilu Ishiagu ni agbegbe Ivo ni Ipinle Ebonyi.Iṣẹ Iṣẹ rẹ Okorie wọ Nollywood ni ọdun 2009, lẹhin ọdun mẹ́wàá nibi ifẹmeric fun ile-iṣẹ ose kan.. | wikipedia | yo |
Fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ti kópa ní SinSinlọ́wọ́ ní ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà wá látọwọ́ Stanley Egbonini tí Ifeanyi Ogbonna sì jẹ́ olùdarí rẹ̀, tó sì ń ṣàfihàn Chigozie atuyá15, Nonso Diobi, Yemi Blaq àti Oge Okoye.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹbi iwe-iroyin Pulse Nigeria ti ṣe sọ di mimọ, o di gbajumọ lẹhin ti o kopa ninu ere Holy Serya.. | wikipedia | yo |
Òun náà sì ti sọ di mímọ̀ pé ó wu òun láti kọ orin ìhìnrere ní ọjọ́ iwájú.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2014, iwe iroyin Vanguard ṣe apejuwe rẹ gẹgẹbi ọkan ninu “awọn oṣere ti awọn eyan n wa julọ” ni Nollywood.. | wikipedia | yo |
Bákan náà, ìwé ìròyìn The Nation náà tún ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́bí “gbajúmọ̀ òṣèré” tí ó máa ń túmọ̀ àwọn ipá rẹ̀ pẹ̀lú ìrọ̀rùn.. | wikipedia | yo |
O tun ṣalaye wipe oun ni ipinnu lati maa gbérejade.igbẹ aye rẹ o ti ṣe igbeyawo o si ti ni ọmọkunrin kan.. | wikipedia | yo |
Ninu atẹjade iwe iroyin Dailyt, o ṣalaye pe igbagbogbo ni oun maa n ṣe igbiyanju lati ya ẹbi rẹ ya awọn oniroyin.. | wikipedia | yo |
Nigbati ó ń sọ̀rọ̀ lórí ìbálòpọ̀ obìrin sí obìrin ní Nàìjíríà, ó ṣàlàyé pé òun kò faramọ, pàápàá nítorí wípé àṣà wa kọọ́.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Bimbo Manuel tí wọ́n bí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù kẹwàá ọdún 1958.. | wikipedia | yo |
jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé tí wọ́n yàn án fún òṣèré tó peregedé jùlọ nínú àmì-ẹ̀yẹ 2013 Nollywood Movies Awards ní ọdún 2013.Iṣẹ́ rẹ̀wọ́n bi Bimbo ní ìpínlẹ̀ Èkó ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akàròyìn ní orí ìkànì Rédíò ti Ìpínlẹ̀ Ògùn (ọgbc) , tí ó sì tún dára pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ amóhùmáwòrán-máwòrán ti ìpínlẹ̀ Ògùn (Oghit) gẹ́gẹ́ bí akàròyìn bákan náà, lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ eré oníṣe ti Tíátà, ní University of Port Harcourt Before commencing His Acting Career in 1986àwọn àṣàyàn eré rẹ̀tan with me (2010) & Zeros (2012) (2013)Dazzling Mirage gé (2014) Yunifásítì Caesar (2014) October 1 (2014) Hell (2015) juwọ́mi (2015) Days (2016) Banana Island Ghost (2017)eré Ori ẹ̀rọ amo-máwòrán Fuji House of Commotion Castle and Castle and Àwọn Ìtọ́kasí Yunifásítì20th-Century Nigerian Malé Actors-Century Nigerian Malé Actor Ènìyàn Alààyè Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1958 Actors From Lagos Ma Ma Mímọ́Àpótíversity Harcourt of Port Harcourt in Yorùbá Cine – Ma | wikipedia | yo |
Ọ̀rọ̀-orúkọ ni èdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-orúkọ ni ọ̀rọ̀kọ́rọ̀ tí a lè lò gẹ́gẹ́ bí i Olúwa fún ọ̀rọ̀ ìṣe, àbọ̀ fún ọ̀rọ̀ ìṣe àti àbò fún ọ̀rọ̀ atọ́kùn.. | wikipedia | yo |
ọ̀rọ̀-orúkọ ni ọ̀rọ̀kọ́rọ̀ tí ó lè dúró gẹ́gẹ́ bí i ìdánimọ̀ fún ènìyàn, ẹranko, ibìkan, tàbí nǹkan.. | wikipedia | yo |
Tí a bá ronú sí àwọn ọ̀rọ̀ tí ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ àti ọ̀rọ̀ àfarajórúkọ máa tọ́ka sí a ma rí pé ọ̀rọ̀-orúkọ ni wọ́n.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Chioma Okoye jẹ oṣere, onkọwe ati agbéréjáde ti o wa lati Ilu Agulérí-O, eyi ti o n bẹ ni ijọba agbegbe ti Iwọ-oorun Anambra, orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu fíìmù Nollywood tó lé ní 100 láti ìgbà tí ó ti bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2002.. | wikipedia | yo |
Lẹhin gbigba ọpọlọpọ awọn ami-eye, Chioma ti di awokọṣe ninu idi-iṣẹ fiimu Nollywood.. | wikipedia | yo |
O jẹ alakóso Purple Ribbon Entertainment.ibẹrẹ aye ati Eko rẹ a bi Chioma ni Ilu Kaduna nibi ti o dagba si pẹlu awọn ẹbi rẹ.. | wikipedia | yo |
Orúkọ ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Okoye Naomi, bẹ́ẹ̀ sì ni orúkọ bàbá rẹ̀ (oloogbe) jẹ́ alàgbà Joseph Okoye, ẹni tí ó kú ní oṣù Kẹẹ̀rin Ọjọ́ Ọgbọ̀n, ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Chioma lọ si ile-iwe Faith Nursery and Primary School ní Ìpínlẹ̀ Kaduna ati Christ the King Seminary Nobi ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa, o lọ si Yunifasiti Ilu Eko nibiti o ti keeko itan-akọọlẹ.iṣẹ iṣẹ rẹ Chioma bẹrẹ iṣẹ ere ṣiṣe nipasẹ pẹ̀tẹ̀ Edochie ti o jẹ aburo baba/iya rẹ.. | wikipedia | yo |
O ri anfani yii ni igba kan ti o tele pẹ̀tẹ̀ Edochie lọ si ibi ti wọn gbe ṣe ipese ere.. | wikipedia | yo |
Ipa akọkọ rẹ waye ninu fiimu No shaking, eyiti o ṣe ni ajọṣepọ pẹlu awọn oṣere bii Victor O’múra ati Sam Loco Efe.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa lo tun kopa ninu ere Nothing Spoil pẹlu ajọṣepọ Chinedu Ikedieze, Osita Iheme, ati Uche Ogbuagu.. | wikipedia | yo |
Ó gbé àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ jáde tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Aṣọ-ẹbí Girls.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti o ti han ninu ọpọlọpọ awọn fiimu to lorukọ, ṣiṣe ifihan ninu fiimu Abuja Connection (2003) mu iranlọwọ ba okiki rẹ nidi iṣẹ fiimu.Àṣàyàn Awọn ere Wbaa ami-eye rẹàwọn Ìtọ́kasí Awọn Eniyan Alààyèawọn Ọjọ́ìbí ni 1983awọn oṣere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oge Okoye (tí a bí ní 16 Oṣù kọkànlá, Ọdún 1980) jẹ́ òsèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ilu Lọndọnu ni a bi Oge Okoye si ki o to di pe o gbero lati wa gbe ni Ilu Eko pẹlu awọn ẹbi rẹ.. | wikipedia | yo |
Ó parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlú Lọ́ndọ̀nù ṣááju kí ó tó wá sí Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Nigbati ó padà sí Nàìjíríà, ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ University Primary School ní ìlú Enugu, kí ó tó tún wá lọ sí Holy Rosary College fún ètò-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ .Ó parí ilé-ẹ̀kọ́ gígai Yunifásítì Nnamdi Azikiwe, ti ìlú Awka pẹ̀lú Oye ní Eré Tiata .. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ́ ile-iṣẹ fiimu ti Naijiria ti a mọ ni Nollywood ni ọdun 2001.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn tí ó kópa nínu fíìmù 'Spanner' ní ọdún 2002 pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Chinedu Ikedieze tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí 'Aki' nídi iṣẹ́ fíìmù ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe igbeyawo ní ọdún 2005 pẹ̀lú ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ Stangley Duruó tí wọ́n ti jọ ń bá ara wọn bọ̀ fún ìgbà pípẹ́, ṣùgbọ́n àwọn méjéèjì ti padà ṣe ìpinyà ní ọdún 2012 lẹ́hìn ọmọ méjì tí wọ́n ní fún arawọn.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006, ó rí yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ African Movie Academy ní ẹ̀ka ti “amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ” fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù “Eagle's pẹ̀lúo tún jẹ́ olùgbéréjáde àti afẹwàṣiṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó ti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àtẹ̀jáde fún Oge ṣíṣe àti àwọn ìkéde ìpolówó ọjà lórí tẹlifíṣọ̀nù.. | wikipedia | yo |
O ti fi igbakan jẹ aṣoju ipolowo ọja fun awọn ile-iṣẹ bi Globacom ati MTN_Nigeria, awọn mejeeji jẹ ile-iṣẹ ti Naijiria to n ri si ibaraẹnisọrọ lori ẹrọ.. | wikipedia | yo |
.Akojọ awọn sinima agbelewo rẹ Spanner (2002) Blood Sister (2003) Forever Yours (2003) Handsome (2003) Magic Love (2003) My Command (2003) Sister Mary (2003) Arsenal (2004) Beautiful Faces (2004) i believe in You (2004) Oyecent Girl (2004) .. | wikipedia | yo |
toô late (2005) Beyond Passion (2005) Black Bra (2005) Crazy Passion (2005) Desperate Love (2005) Eagle's Democratic (2005) Emotional Battle (2005) Everyn Single Day (2005) Face of Africa (2005) .. | wikipedia | yo |
UKriaria Friends & Lovers (2005) The Girl Is Mine (2005) It's Juliet Or No One (2005) The King's Son (2005) Ṣẹ́du Me (2005) Orange Groove (2005) Paradise to Hell (2005) Shock (2005) To Love And Live Again (2005) Trinity (2005) Trouble Maker (2005) War Game (2006) The snake Girl (2006) Blackbery Babes (2010) Sinru Sinful Game Game Town (2014) Eré tẹlifíṣọ̀nù Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1980àwọn Ènìyàn Alààyè Àwọn Òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó rí yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ Africa Movie Academy fún ẹ̀ka ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó dára jùlọ.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2013, ó kópa nínu eré Golden Eg, pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Justus Esiri.. | wikipedia | yo |
Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan ti ọdun 2015, o sọ di mimọ wipe fiimu Duplex ni fiimu ti o pe oun nija julọ.. | wikipedia | yo |
Nigbati o n sọ̀rọ̀ lori iru ipa ti ko lẹ́ẹ̀ ṣe ninu fiimu, o ṣalaye wipe oun ki yoo kó ipa oníhòhò.. | wikipedia | yo |
Okpoko ti tun ṣafihan ninu ọpọlọpọ awọn ere Telifisonu ti Naijiria to fi mọ Dear Mother, Clinic Matters, Neta, University Mafias, Sorrowful Child, Sacricri the Baby, Red Scorpion ati Baby Oku.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, òun pẹ̀lú Majid Michel àti Beverly Naya jọ kópa nínu eré The Madman I Love.. | wikipedia | yo |
Okpoko tun jẹ ọkan ninu awọn oṣere ti o kopa ninu ere Uche Jombo kan ti akole rẹ n jẹ Good Home (2016), pẹlu ajọṣepọ Okey Uzoeshi ati ṣeun Akindele.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri ṣíṣe àlàyé gbígbé ọmọènìyàn fi ṣiṣẹ́, pẹ̀lú bí ó ti ṣe ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà.Igbe ayé rẹ̀ Okpoko jẹ́ ọmọ abinibi ti Ìpínlẹ̀ Anámbra.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Jàmáíkà.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe igbeyawo, o si ti ni àwọn ọmọ mẹta.Àwọn itọkasi àwọn eniyan alààyèàwọn oṣere ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn eniyan Alààyè).. | wikipedia | yo |
Agbolérí Okujaye (ti a bi ni ọjọ kerindinlogun oṣu kaarun ọdun 1987) jẹ oṣere orilẹ-ede Naijiria, olugberejade, onkọwe ere, onijo, akọrin ati marun.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2009, o jawe olubori nibi kikopa ninu eto telifisonu ti Amstel Malta Box Office (AM).. | wikipedia | yo |
Àwọn èyàn máa n pèé ní Little Genevieve nítorí wípé ó fi ojú jọ òṣèré Genevieve Nnaji.. | wikipedia | yo |
O gba ami-eye ọdọmọde oṣere ti o dara julọ nibi ayẹyẹ ti ẹjọ́ẹjọ ti Africa Movie Academy Awards.Ìgbé ayé rẹ a bi Okujaye ni Ilu Benin si ọwọ baba ti o jẹ ọmọ Ipinle Delta ati iya ti o jẹ Ipinle Edo.. | wikipedia | yo |
Okujaye ni ikẹhin ninu àwọn ọmọ marun-un ti obi rẹ̀.. | wikipedia | yo |
O ti sọ nigbagbogbo pe awọn obi oun fẹ ki oun keEko isogun nitori pe ọpọlọpọ awọn oṣiṣẹ ìsọgun wa ninu ebi rẹ.. | wikipedia | yo |