cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ní ọdún 2006, ó gba àmì ẹ̀yẹ Standard Bank Young Artist Award fún ipa tí ó kó nínú dírámà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó wà láàrin àwọn èèyàn mẹẹdọgbọn tí wọ́n yàán kalẹ̀ fún Rolex Mentor Protété Arts Initiative.ní ọdún 2011, eré butcher Brothers tí ó ṣe gba àmì ẹ̀yẹ láti ọ̀dọ nalẹ̀dí Awards.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Wàv Jotsane (bíi ní ọjọ́ kẹwàá, Oṣù Kẹjọ ọdún 1977) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa Celia kúnf tí ó kó nínu eré SIslam Saam.. | wikipedia | yo |
O lo si ile eko Prudebs Secondary School ki o to tesiwaju si ile eko giga ti Tampere University of Technology.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Stephanie Nopalov (Bii ni ojo kokandinlogbon osu Kẹwàá odun 1991) je osere ati agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orile ede South Afrika ti o gbajumo fun ipa ti o ko ninu ere scandal ati Shuga.O lo si ile eko giga ti University of Johannesburg.. | wikipedia | yo |
O jẹ ikan laarin awon atọ́kùn eto omode ti akori re je CRaza-e.. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa Ingrid nínu eré scandal ní ọdún 2015.Ó fẹ́ Hungani Nlolov ní Oṣù Kejì Ọdún 2019.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2007, o gba ẹbun osere to dara ju lọ ninu Efe lati odo South African Film and Television Award.. | wikipedia | yo |
Ó bi ọmọ méjì tí orúkọ wọn jẹ́ kakópa àti Nlẹ̀dí.Àṣàyàn àwọn eré àkò Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Antoinette Piyínrr (bíi ní ọdún 1961) jẹ́ olórin, akọ̀wé àti òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà.Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Stellenbosch níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ dírámà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ìtàn ìgbésí ayé àwọn èèyàn akíkanjú ní orílẹ̀ Adugbọ̀n tí ó ma n sọ.. | wikipedia | yo |
O je omo ise fun Joannes Willemse lati odun 2001.. | wikipedia | yo |
Láti ọdún 2003 ní òhun àti Johannes Willemse tí ma ṣe atọ́kùn ètò amọ̀rẹ̀ láìjẹ́kers lórí radìí (Radio Sonder Grensense).. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, ó kó àrùn cerebral malaria lẹ́yìn ìgbà tí ó lọ sí orílẹ̀ ède Mali.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Chief Clav Chukwura (ti oruko ibi rẹ je Clara Nneka Oluwatoyin Folashade Chukwurah; 24 Osu Keèje Ọdun 1964) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Olùfẹràn Ọmọ.Iṣẹ́ iṣẹ́ àti ẹ̀kọ́ rẹ ó ka ilé-ìwé alakọbẹrẹ rẹ̀ ní ìlú Èkó ṣáájú kí ó tó lépa ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ ní Queen of the Rosary College, ní ìlú Onitsha.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa lo tẹsiwaju lati keEko Iṣẹ oṣere ni Ile-ẹkọ giga Obafemi Awolowo .O gba oye Aṣoju alafia ti Ajo Agbaye fun iṣẹ Alaanu rẹ ni gbogbo ile Adunlawo.O bẹrẹ iṣẹ oṣere rẹ ṣiṣẹ ni ọdun 1980 ṣugbọn o di gbajumọ nigbati o kopa ninu ere kan ti akọle rẹ jẹ “Mirror in the Sun” | wikipedia | yo |
Òun ni ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ láti gba àmì ẹ̀yẹ fún ti òṣèré ọdún tó dára jùlọ níbi ayẹyẹ àjọ̀dún fíìmù ti ọdún 1982 ti FESPACO ṣe agbátẹrù rẹ̀ ní Bùrkínà Fasọ̀.Igbe ayé rẹ̀ Chukwura jẹ́ ọmọbìnrin kan ṣoṣo nínu ìdílé eleyan mẹ́rin tí a bí ní 24 Oṣù Keèje, Ọdún 1964.. | wikipedia | yo |
Oun ni iya Clarence Peters, ẹnìkan ti n se oludari fidio orin .. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ará ìlú Anámbra .ní ọdún 2016, Chukwura ṣe ìgbeyàwó fún Eeta pẹ̀lú Anthony Boyd, ó sì yipada sí ÌGBÀGBỌ́ àwọn ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ ti oko titun rẹàwọn eré tẹlifíṣọ̀nù tí ó ti kópa Bello's Way (1984) Mirror in the Sun (1984) Ripples (19891989) Super Story (2001)àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Fifi Force (1986) Money Power (1982) Farewell to Babylon (1979) Yemọja Apaye Glamour Girls 2 Remarkable Night Igbotic Love Forbidden choice caught in the Act. | wikipedia | yo |
Abuja Connection Egg of Lifeàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyẹ̀àwọn Ọjọ́ìbí ní 1964.. | wikipedia | yo |
Celeste ńtúli (bíi ní kẹẹdọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1978) jẹ́ òṣèré àti aláwàdà ní orílẹ̀ ède South Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi olórí fún Efe ní ilé Zulu.Wọn bíi ńtúli ní ìlú Empangeni níbi ó ti gba ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Oun ni ọmọ kẹfa laarin àwọn ọmọ mẹjọ ti àwọn òbi rẹ bi.. | wikipedia | yo |
O lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Durban University of Technology.Iṣẹ́ ní ọdún 2005, ó ṣe ẹ̀fẹ̀ àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ilé ìjọ́sìn ní Durban.. | wikipedia | yo |
O to se orisirisi Efe, laarin awon ayeye ti o ti se Efe ni Blacks only Comedy showcase ni odun 2010 ati 2012, sa comic's choice awards 2012.O ti kopa ninu awon ere bii Isibáyà, 10 Days in sun city, Lockdown, Looking for Love ati trippin with skhu.Ni odun 2014, o gba ami eye Best Supporting Actress lati ọdọ Golden Horn Award.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, wọ́n yàán fún oríṣiríṣi àmì ẹ̀yẹ láti Odò Comics' Choice Awards.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye flying solo ati Comedy G Award lati Odò Savanna Comics Choice Awards.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Zola Nombona (Bii ni ojo kẹwàá Oṣu Kẹta ọdun 1992) jẹ oṣere ni orile edè South Afrika ti o gbajumọ fun ipa Shado ti o kọ ninu ere Intersexions ni ọdun 2013.O lọ si Ile Eko Victoria Girl's High School No Ilu Ghámìms ki o to wa lọ si Ile ẹkọ giga ti wits University nibi ti o ti gboye ninu imo Dramatic Arts.Iṣẹ Nombona koko kopa ninu ere Interse-omidan ni ọdun 2013, ere naa si soro nipa arun Komi HIV/AIDS.. | wikipedia | yo |
O ko ipa Monde ninu ere Lockdown ati Zee ninu ere Number Nuyan.àṣàyàn awon ere itọkasi itọkasi.. | wikipedia | yo |
Elizabeth Omowunmi Tekovi Da-Silva (ti a bi ni Oṣu KeEfa Ojo 10, ọdun 1978) jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria ati Togo ti o maa n saba kopa ni ọpọlọpọ igba ninu fiimu Yoruba ti Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, wọ́n yan Da-Silva fún àmì ẹ̀yẹ City People Movie Award fún ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó dára jùlọ (ẹka ti eré Yoruba) níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018 bákan náà, ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards.ibẹrẹṣe ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bi Da-Silva sí ọwọ́ àwọn òbí tí n ṣe ará Togo ṣùgbọ́n tí wọ́n ń gbé ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
A bi ní agbègbè tí a mọ̀ sí Obalende ní ìpínlẹ̀ Èkó níbití àwọn òbí rẹ̀ gbé, níbẹ̀ lọ sí ti lo ìgbà èwe rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú àwọn oníròyìn kan lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ṣàlàyé pé ìlú Èkó dá gẹ́gẹ́ bí ilé òun, ó sì sọ nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò náà pé òun wá láti ilé olórogún.. | wikipedia | yo |
Da-Silva lọ si Ireti Grammar School fun eto-ẹkọ iwe mẹwa rẹ, o si tẹsiwaju lọ si Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Eko nibi to ti gba oye-ẹkọ B.Sc.iṣẹ iṣe rẹ ninu ifọrọwanilẹnuwo kan Da-Silva ṣalaye pe oun bẹrẹ si nife si lati darapọ mọ ile-iṣẹ fiimu ti Yorùbá ti Naijiria ni akoko ti oun wa ni ile-iwe girama.. | wikipedia | yo |
Nígbà náà lòlòlò bẹ̀rẹ̀ sí kópa nínú àwọn eré ti ilé-ìwé.. | wikipedia | yo |
Da-Silva ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu awọn oniroyin The Punch ṣalaye pe oun ko ipa akọkọ ni ile-iṣẹ fiimu Yoruba ti Naijiria ni ọdun 2004 nipasẹ iranlọwọ Iyabo Ojo.. | wikipedia | yo |
Da-Silva di gbajumọ oṣere lẹhin ti o ko awọn ipa gboogi ninu fiimu meji kan; akọle akọkọ ni wakati mẹta latọwọ Wale Lawal ati fiimu kan ta pe akole rẹ ni Omidan latọwọ iyabóo Ojo.Da-Silva ni ọdun 2012 ṣe akọkọ igberejade rẹ pẹlu fiimu ti akọle rẹ jẹ Mama Insurance, eyiti o ṣe ifihan Ayo Mogaji, Lanre Hassan, Ojo, Ronke Ojo, ati Doris Simeon .igbẹ aye rẹ da-Silva jẹ ọmọ orilẹ-ede Naijiria nipasẹ bibi ati ọmọ orilẹ-ede Togo nipasẹ awọn obi rẹ.. | wikipedia | yo |
Da-Silva ti ṣalaye ipinlẹ Eko bi ile rẹ, ṣugbọn o si ni adiṣọkan lati ni Faranse pẹlu awọn mọ̀lẹ́bi rẹ ni Togo.. | wikipedia | yo |
Da-Silva ni ọdun 2013 yipada lati Kristẹni si Islam.Awọn ami-ẹyẹ ati yiyan rẹipa Da-Silva lorukọ, Bukky Wright gege bi awokose rẹ ninu ile ise fiimu Yoruba ni Naijiria o si sọ pe oun ti nipa lori, ọna isere rẹ ni pataki.Awon fiimu rẹ ti a yanọrẹ l'Ore nwoto (2007) Omidan desireitanjẹ Insurance Kanmáwọ̀máwọ̀d'Mama Insurance Awọn itọkasi Awọn Ọjọ́ìbí ni 1978àwọn Eniyan Alààyè.. | wikipedia | yo |
'yul Edochie''' (ti a bí ni yul Chibuike Daniel Edochie '''Ọjọ́ keje oṣù kíní ọdún 1982)jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,òun sì ni a dárúkọ lẹ́yìn olókìkí òṣèré ará ìlú Russia kel Bry5BFR.. | wikipedia | yo |
O wa lati Ipinle Anambra Naijiria, ọmọ osere Naijiria pẹ̀tẹ̀ Edochie.. | wikipedia | yo |
ó lọ sí Yunifásítì ti Port Harcourt, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor ní eré fíìmù àwòrán ní iṣẹ́ iṣẹ́ ìgbésẹ̀.Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ Yul lọ sí ilé-ìwé alakọbẹrẹ ọmọde Ọjọ́ Lillilli àti Ile-iwe Robinson Street alakọbẹrẹ School, Enugu laarin 1984 àti 1992.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun mẹfa wọ̀nyẹn o lọ si Marist Brothers 'Rayanjúte, Uturu, Ile-iwe Secondary University Enugu , ECumenical Community Secondary School Enugu ati New Kiriven Boys Secondary School Enugu ni ṣókí.igbesi aye ara ẹnio ti ni iyawo to orukọ rẹ gun jẹ́ May Aligwe o si ni ọmọkunrin mẹta ati ọmọbinrin kan.Iṣẹ-iṣẹ o darapọ mọ Nollywood ni ọdun 2005 ninu fiimu akọkọ rẹ ti akole rẹ ni "The Exjakinis" lẹgbẹẹ alaisi ju Esiri e ati Eneli Elewa.. | wikipedia | yo |
ó ní àdéhùn rẹ̀ ní ọdún 2007 lẹ́yìn ìfihàn pẹ̀lú Genevieve Nnaji àti Desmond Elliot nínú fíìmù náà "Wind of Glory".Àwọn ìṣọ̀wọ́ míìranílé-ẹ̀kọ́ gíga yul Edochiẹni ọdún 2015, YUl Edochie lọ sí ilé ẹ̀kọ́ fíìmù ní ẹ̀kọ́.. | wikipedia | yo |
O ṣe ifilọlẹ ile-ẹkọ giga bi abajade ti didara ati àmòdájú ti awọn oṣere ati oṣere ti nbọ.. | wikipedia | yo |
Ile eko bi o ti ṣalaye nipasẹ rẹ ni o yẹ ki o ko iran ti n bọ ti Nollywood olukopa ati awọn oṣere.. | wikipedia | yo |
ilé-ẹ̀kọ́ gíga n fun àwọn ènìyàn abínibí ní àyè lati ṣafihan si ile-iṣẹ fiimu ti Naijiria.ìṣèlú ni ọjọ kerinla ti oṣu keje 2017, yul Edochie sọ ipinnu rẹ o dije fun ipò Gómìnà ti ìpínlẹ̀ Anambra.. | wikipedia | yo |
Ìkéde yìí ni a ṣe ní ìfojúsọ́nà ti ibẹ̀yẹ̀wò aó kéré láti sáré tí ó kọjá nípasẹ̀ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìjọba àpapọ̀ ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ikede naa ni a se ni sise ni ojo kejilelogun ti Oṣu Kẹjọ ọdun 2017, nigbati o mu Fọọmu yiyan fun ẹgbẹ oselu "Democratic Peoples Congress" ati pe ni ti o ni Asia ati oludibo Gomina ti ẹgbẹ lati dije fun Gomina ti Ipinle Anambra.Awọn ẹ̀bùnàwọn Akojọ eretẹlifisiọnu The Palace (soap (soap). | wikipedia | yo |
Royal Castle (Soap opera).Tinsel (TV series) (Soap opera)Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ọnà asopọ Ita Yul Edochie Personal Website yul Edochie Official websiteUniversity of Port Harcourt alumniàwọn ènìyàn AAlààyèIgbo Television personalities Actors from Anambra StateÀwọn Ọjọ́ìbí ní 1982Igbo Malé Actors-21st Nigerian Malé Actors Film film Actors | wikipedia | yo |
lindilẹ̀ Ndanga (Bii ni ojo ketalelogun Oṣu Kẹfa ọdun 1972) jẹ oṣere ni orilẹ edè South Afrika ti o gbajumọ fun ipa Ruby DiKobe ti o kọ ninu ere Generations.Nodin dagba si Ilu Durban, Iya baba rẹ lo si tọju rẹ.. | wikipedia | yo |
NodanGala ti bi ọmọ meji.Iṣẹ Nodanga sise pelu Yceum Theater ni ilu London ni odun 2001.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu eré Generations láti Oṣù Kẹfà Ọdún 2011 di Oṣù kejìlá Ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
O ti farahan ninu ere Izulu lami ni odun 2008 ati The Lion King.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
VatiSwa ńdára (bíi ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹ̀sán-án Ọdún 1970) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní orílẹ̀ ède South Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí sí ìlú Mthatha ni ilé eastern cape.Ní ọdún 1994, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn ní orí Rdìí transkékéì.. | wikipedia | yo |
O ti sise pelu awon ile ise Radìío bii radio Bob, káyà FM, Metro FM, 5FM ati Highveld síbís.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe nígbà tí wọ́n ní kí ó kó ipa má’mfúndísì nínú eré Generations.Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù Kẹwàá ọdún 2019, ó kọ lẹ́tà sí Nathi Mthwá tí ó jẹ́ aṣojú ìjọba lórí ọ̀rọ̀ àṣà àti ìṣe, lẹ́tà náà sọ nípa bí àwọn ilé iṣẹ́ Connie Ferguson àti Shona Ferguson ṣe ń fi ìyà jẹ àwọn òṣèré.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Generations Gaz'lam Salvation Nothmi Home Affairs Society shooting Stars 90 Plein Street ìhà ìhà Inzwe Muvkíkùn igazi Ithem Ithem.. | wikipedia | yo |
Leorigo mot (Bii ni ojo kejidinlogbon osu kerin odun 1975) je osere ati olorin ni orile ede South Afrika ti o gbajumo fun ipa Letti Matabane ti o ko ninu ere isindì lati odun 1998 titi di odun 2008.. | wikipedia | yo |
Ó jáde láti sọ̀rọ̀ ní ọdún 2011 pe ohùn ní àrùn kògbóògùn HIV.Ó dàgbà sí ìlú Meadowlands, ó sì lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Technikon Pretoria níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ ọ̀rọ̀ sísọ àti dírámà.. | wikipedia | yo |
Ni igba ti o wa ni ọmọ ọdun marun-un, o kopa ninu ipolowo lori telefisonu, ibẹ̀ si ni wọn ti fun ni orukọ inagi námà ya Nku.O kopa ere bíkòbájẹ́ - where the Soul resides .go ku ni ọjọ ogun ni oṣu sinu igbeyawo 2014.Àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
tùmí mọrake (Bii ni ojo kejilelogun Oṣu kejila ọdun 1081) jẹ oṣere, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati Akowe ni orile ede South Afrika.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Áfríkà tí ó ma gbé eré Efe rẹ̀ sí orí Netflix.. | wikipedia | yo |
Òun sí obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma ṣe atọ́kùn fún ètò Comedy Central presents ní ilẹ̀ Áfríkà.Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti wíts University níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ àà.Iṣẹ́ ní Oṣù Keje ọdún 2005, ó darapọ̀ mọ́ àwọn tí ó ma ṣe ìtara àti Efe.. | wikipedia | yo |
Láàárín àwọn ibi tí ó ti ṣe àwàdà ní heavyweights Comedy Jam, Blacks Only, Have a heart, just because Comedy Festival, the tshwane Comedy Festival, the lifestyle sa festival àti old mutual Comedy Ents.Ó ti ṣe atọ́kùn fún àwọn ètò bíi our Perfect wedding, red cake àti wţf8C.òun ni ó kọ ìwé and then Mama said.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó gba àmì ẹ̀yẹ entertainer of the year láti ọ̀dọ̀ speaker of note award.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, ó gba àmì ẹ̀yẹ Excellence in Comedy láti ọ̀dọ mbọ̀ko Women in Arts Award.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ aláwàdà tó dára jù lọ láti ọ̀dọ You Kodcular Awards.àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣe Skin kọta Life Crisis Soul Buddyz Looso Connmeng High Rollers Laugh Out Lod Rockville Soul Buddyz the Queen the Bantu Hour Seriously Single tùmí or Not Atu (Netflix) tùmí jẹ́ ìyàwó fún MPho Oosi-fu, wọ́n sì ti bí bí ọmọ mẹ́ta.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Uche EleN(ti a bi ni ọjọ́ kẹrìnlá, oṣu keje, ọdun 1986) jẹ oṣere ará Ilu Nàìjíríà ati akọrin.. | wikipedia | yo |
Ati ọ̀táJaa ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́bí ọ̀kan ninu àwọn ojú ti ó ṣe déédé jùlọ ni ilé-iṣẹ́ fiimu ti Nàìjíríà lati àkókò ti ó wà ni ọdún 2001 titi di ọdún 2010 nígbàtí ó gba ìsinmi lati ile-iṣẹ ere idaraya ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
gẹ́gẹ́bí ìwé ìròyìn Vanguard Elendu ti ṣe ìfihàn nínú fíìmù tí ó ju ìgbà ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ ẹlẹ́ndu ni a bí ní ìpínlẹ̀ Ábíá èyítí ó wà ní agbègbè ila-oorun gúúsù ila oòrùn ti Nàìjíríà, tí ó borí púpọ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn igbó ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
èléwẹ̀ ní ọmọ àkọ́kọ́ tí àwọn òbí rẹ̀ bí àti pé ó ní àwọn arákùnrin àbúrò mẹ́ta tí gbogbo wọn jẹ́ akọ.. | wikipedia | yo |
bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ìlú tí ó ti fẹ̀yìntì àti oníṣòwò lákokò tí ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́.. | wikipedia | yo |
oye ni awon ibatan kariaye lati Yunifasiti ti Ipinle Imo.Iṣẹ-iṣẹ EleN darapọ mọ ile-iṣẹ fiimu ti Naijiria ti a mọ ni Nollywood ni ọdun 2001.. | wikipedia | yo |
Arabinrin yi bẹrẹ iṣẹ osere rẹ nipa ifihan ninu fiimu ti akole re ni "Fear of the unknown" Elendu se isinmi pipe lati sise nitori igbeyawo ati ise yii bajẹ ti iyọ kuro ati idaduro rẹ ọmọ bi ohun oṣere.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2015 ó ní ìfipamọ́ ipa olùdarí nínú fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ “Ada Mbano.” Fíìmù yìí ni Ayase “Which” tun tan iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ “Nọ̀gá Àdu nínú Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú The Sun jíròrò lóri àwọn ìgbìyànjú asan rẹ̀ láti padà sí ilé-iṣẹ́ fíìmù Nollywood lẹ́yìn tí ó padà kúrò ní ìsinmi iṣẹ́.. | wikipedia | yo |
ó ṣàlàyé síwájú sí ipa pàtàkì ti fiimu “Ada Mbano" àti ipa rere tí ó ní lórí iṣẹ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò náà ó ṣe àkópọ̀ ipa ti fíìmú lórí iṣẹ́ rẹ nípa sísọ “Fiimu ti o ṣe ifilọlẹ mi padà ni” ada Mbanrio ""igbesi aye ara ẹni Eledu, botilẹjẹpe o ti kọ iyawo rẹ silẹ bayi, o ṣe igbeyawo ni Oṣu Kini ọdun 2012 ni Ilu ti Owerri, Ipinle Imo si Walter Ògochukwu Igweṣíṣàṣàròmba ati pe awọn mejeji ni ọmọ meji papọ̀ awọn méjẽjì jẹ obinrin.. | wikipedia | yo |
Elen ti ni ipa ninu ọpọlọpọ awọn ijamba ọkọ ayọkẹlẹ eyiti ọkan ninu iru bẹẹ fi i silẹ mọ.ilera elendu ti so ni gbangba nipa ipo iṣoogun ti a pe ni EnọbatylKristẹni, aisan ti o ti ni ayewo pelu.aṣayan awon Akojọ ereNigerian Girls (2009)The Rain Makers (2009) Sisters (2009) Zv Oyer (2008) of my heart (2008) O wanna Be a Player (2008) It Up (2008) Girls (2008) The Ver (2007) Bull & Roṣẹ́kàte (2007)lost in the Junga (2007) Rib (2007)Most Wanted Bachelor (2007) of Evil (2007) Oludara Testament (2007) E- (2007) Bond (2007) rù (2006) Cross (2006) of the Ghost ( [2006) Culme (2005)o ↑ (2005) Risk (2005) To Love and Live (2005) On Top (2005) Awọn Ìtọ́kasí (Awon Ona ìta àwọn ènìyàn Ìdara 2006 ni 1980-FM Act-21st Nigerian Act gbo Act gbo People.. | wikipedia | yo |
Omowumi Dada jẹ́ oṣere ọmọ Nàìjíríà, ti o gbajumọ julọ fun ipa rẹ gẹgẹ bi Folake ninu ere Telifisonu ti M-Net kan, Jemeji.. | wikipedia | yo |
ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó kópa nínú fíìmù èdè Yorùbá kan, Somewhere in the Dark ní ọdún 2017, èyítí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti Fíímù àbínibí tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ AMVCA Awards ti ọdún 2017, fíìmù náà sì sọkún fa yíyan rẹ̀ fún ti amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ (ẹ̀ka èdè Yorùbá) níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ní ọdún 2017 bákan náà.ibẹrẹ aye rẹ a bi Dada ni Ìpínlẹ̀ Èkó, nibi ti o ti lọ si Ifako International Nursery and Primary School fun eto ẹkọ alakọbẹrẹ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò náà, ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àṣà ilẹ̀ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
O tẹsiwaju lati lọ si Ile-iwe Command Day Secondary School, to wa ni ilu Oshodi, fun eto-ẹkọ girama rẹ ṣaaju ki o to lọ keEko Creative Arts ni ile-iwe giga University of Lagos.Dada bẹrẹ iṣẹ oṣere rẹ pẹlu ṣiṣe awọn ipa kekere ni awọn ere ipele ni akoko igba ti o wa ni Ile-ẹkọ giga.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ ipa gboogi tí ó se lóri ìpele wáyé nínú eré Mọ́remí Ajasoro, èyítí Femi òkè ṣe olùdarí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013, o bẹrẹ iṣẹ fiimu rẹ pẹlu ipa kan ninu fiimu oya pẹlu ajọṣepọ oṣere Tunji Sotialátakò, lẹhin naa lo tẹsiwaju lati ṣe ifihan ninu awọn fiimu miran to fi mọ fiimu ti Kunle Afolayan dari, Owayewo ni ajọṣepọ pẹlu Patience Ozokwor ati Ayo Adesanya.. | wikipedia | yo |
Dada ti ṣe ifihan ninu ọpọlọpọ ere telifisonu, to fi mọ́ awọn ere EbonyLife bi Married to the Game, Best Friends ati Dere, ere ti n ṣe ìbágba “Cinderella” ti Disney ní ilẹ̀ Afirika.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù MNET tí àkọ́lé R jẹ́ Jemeji, ó sì ti ní àwọn ipa nínú Tinsel, so Wrong so Wright, Needles Eyes, Bella's Place àti àwọn míràn.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1989àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Julius Agwu (bi ni Oṣu Keje, oṣu igbe, ọdun 1973)jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín, òṣèré, olórin àti atọ́kùn.. | wikipedia | yo |
Oun ni alaṣẹ ati oludari iléeṣẹ́ Reellaif limited, music and movie production company.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olùdámọ̀ràn lórí amúlùúdùn àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ajẹmọ́-Ìṣípayá.. | wikipedia | yo |
Òun ni olóú àwọn eré bíi adarí crack ya Cribsbs, Laff 4 Christ's Sake àti Festival of Love.Iìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgbé-ayé àti iṣẹ́ ìlú Port-Harcourt ní Ìpínlẹ̀ Rivers ni won bi sí.. | wikipedia | yo |
Awon obi re ni Oloye Augustine Onisele Anawólẹ̀ ati Arabinrin Mary Aya Bàbà.. | wikipedia | yo |
Ilu Port-Harcourt ti o dagba si ni o ti bẹrẹ o bẹrẹ ere sise lori itage.. | wikipedia | yo |
O ti se opolopo ere ori tẹlifísàn ati awon ere bii Torn (2013), a long night (2014) ati after Count (2011).eko Julius Agole bere eko ni ileile alako ti Ipinle (Eleyen State School) ti o di ileile alako ube ni choba, Ipinle-Harcourt, IpinleHarcourt, Ipinle ti o ti gba iwe-ẹri Eko Alaroko Arabeere.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ ó tẹ̀síwàjú sí ilẹ̀ilẹ̀ Ẹ̀dìrì ti ìjọba ní borokiri, Port-Harcourt, ìpínlẹ̀ Rivers, Nàìjíríà, ó sì padà parí ẹ̀kọ́ Ẹ̀dìrì rẹ̀ ní iléilẹ̀ Gífí Akpor ní Ozọba, Port Harcourt ìpínlẹ̀ Nírá tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí ìdánwò-ẹ̀rí ìdánwò ti ilé ẹ̀kọ́ gíga (West African Senior School Certificate).. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà ní ilẹ̀ilẹ̀ gírámà Akpor ni Ozọba, ó jẹ́ oyè amúlùúdùn àti Ààrẹ Ẹgbẹ́ Eré - Oníṣẹ́, Ẹgbẹ́ Ìjíròrò àti Àṣà.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó pàrí ẹkọ́ sekondiri rẹ̀, ó lọ lo èko tíátà ní ipele ìlọ́lọ́lọ́we ní Yunifasiti Port-Harcourt tí ó sì gbajú eré Ṣímọ̀, ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ eré - ṣsàka ẹkọ́ ẹmọ̀ kan tó àwọn ènìyàn òmú ní 1973 ní 1973-SHel Nigerian Actors-21st Nigerian singers-21st Ọgí Maria.. Ọya gi àwọn tí ó ja ní ọdún * * ní ọdún * * * * * ẹ̀lẹ̀- ní ó dín - oníka ẹràlẹ̀ ní ó pàmọ̀ àwọn oníka ọdún rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ - jáwọ́ ní ọdún ọdún ní Yunifásítì kan * gbajúmọ̀ àwọn ìdá ní pẹ̀lú pẹ̀lú pẹ̀lú ẹ̀rìyàn - tí ó pàmọ̀ kan * lọ ní 1973 ọdún York ní Yunifásítì 2003- ní ó sí gbajúmọ̀ sí gbajú sí pẹ̀lú pẹ̀lú ọdún ọdún ọdún rẹ̀ sí pẹ̀lú ẹrin sí ọdún ọdún ọdún rẹ̀ sí 1973 ní 1973 Ọdún 2003 ní ọdún Mìyàn tí ó pàmọ̀ ẹkọ́ sí ọdún rẹ̀ Oṣù pẹ̀lú ẹ̀kọ́ tí ọdún ọdún ọdún ọdún ọdún náà tí ó sì fi gbajú eré tí ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ kan tí gbajúmọ̀ ẹyà ẹmọ̀ àwọn onímọ̀ àwọn ẹrisì àwọn ìdá ní 1973 ní fi àwọn tí àwọn ọdún àwọn tí tí Leo náà* | wikipedia | yo |