cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Lára wọn ni just not married, flipped ati the Ìléríes.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn 100 tí YNaija yàn gẹ́gẹ́ bi àwọn tó ní ipa jùlọ nínú fíìmù ìlú Nàìjíríà.ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Audu ní ìlú Aawng Navy ní ọjọ́ọ́, ní ìlú Èkó sí bàbá tí n ṣe òṣìṣẹ́ Navy kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Audu Ali Audu àti ìyá tí òún jẹ́ gigi Salamatu Audu.. | wikipedia | yo |
Ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé ìtajà oúnjẹ bẹ́ẹ̀, ó sì tún ṣiṣẹ́ ìpèsè àwọn òun ìyálọ fún ìnáwó.. | wikipedia | yo |
Judith ni awon alájọbí meji ti won se arakunrin Franklin audu ti n se egbon re ati arakunrin aburo kan Abdulmalik audu.. | wikipedia | yo |
Òun ni ọmọ èkejì àti ọmọbìnrin kan ṣoṣo ti àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó wá láti agbègbè Mońnló ti Ìpínlẹ̀ Ẹdó ní Nàìjíríà.Audu lọ sí ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ Navy Town, ọjọ́ọ́, láti ọdún 1988 sí 1993.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà ló lọ sí ilé-ìwé girama ti Navy Town bákan náà láti 1993 sí 1999, níbi tí ó ti gbájúmọ́ àwọn iṣẹ́ Arts.. | wikipedia | yo |
lẹhin náà lọ lọ si ile-iwe giga kan ti o wa ni Badagry ni ọdun 2001 to si gba oye-ẹkọ, eyi ti o lọ lati wọ ile-iwe giga University of Lagos ni ọdun 2002.Ni ọdun 2005, Audu gba oye-ẹkọ B.A ninu èdè Faranse lati Yunifasiti ti Eko.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti o pari Agùnbánirọ̀ (NYSC) re ni Ipinle Kebbi ní ọdún 2007, ó padà sí Yunifasiti ti Èkó láti lépa oyè gíga nínu ìmọ̀ Oro ìlú àti ti Kariaye láti ọdún 2008 sí 2010.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
ISÁGE bishop, tí wọ́n tún pè nílóhùn Lagos tàbí Udo Yes, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé , alábí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Nigeria.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ Iel jẹ́ ọmọ bí bí agbègbè Ibom àti ẹ̀yà ibiO ibi lati ìpín Akwa Ibom Ibom ; | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì tuntun níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ philosophy.. | wikipedia | yo |
Ó ti bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe eré orí-ìtàgé láti ìgbà tí ó yó wà ní ọmọdé, lẹ́yìn tí ó ti dára pọ̀ mọ́ Nollywood ó ti kópa nínu eré tí ó ti tó ojú ún.. | wikipedia | yo |
Eré tí ó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ jáde ní Unílé, eré tí ọ̀gbẹ́ni Emem Isong gbé jáde ní ọdún 2008.ìfowó sí rẹ̀ ó jẹ́ aṣojú Olupol fún àjọ Gganbacom ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìyàndọ́gba ìdọ́gba rẹ̀ Wọ́n yan Imesi sí ipò olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ìyẹn Udom Gabriel Emmanuel lórí Inlani fún Ara ìlú.àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti ÌFISỌRÍ Wnilè àṣàyàn eré rẹ̀ Secondary kópa nínu fọ́nrán kan tí wọ́n tún ní pregnant man man tí isemole tí isemole COVID-9 Role díá-ẹ́ tún tún wọ MC Galaxyíni ní Ìtọ́kasí Guaga from Akwa Ibom 2008 ní Ọjọ́ìbí ní 1981 ní gbogbo ènìyàn Film Actors-21st O Àjàpá Actor of Uyo Ibiwó Ibidọ́gba | wikipedia | yo |
Lilian Esoro tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá Oṣù Kẹta ọdún 1982.. | wikipedia | yo |
jẹ oṣere ori-itage ati sinima ọmọ orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàn án fún ipò òṣèrébìnrin aláwàdà tó peregedé jùlọ nínú àmì-ẹ̀yẹ ti ‘2013 Africa Magic Viewers Choice Awards'.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Ẹ kẹkọ jáde nípa ìmọ̀ ìṣèlú ní Yunifásítì ti Abuja.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ottrélian bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní ọdún 2005, nígbà tí ọ̀rẹ́ rẹ̀ bọ̀vi fún ní àyè láti kópa nínú eré àtìgbàdégbà ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní Clicn Matters, tí ó sì kópa bí nọ́ọ̀sì Abigail nínu eré náà..Ẹ wà lára àtòjọ àwọn òṣèré túnrun tó peregedé jùlọ ní Nollywood gẹ́gẹ́ bí ìwé-ìròyìn Vanguard ṣe ṣe àtòjọ wọn.Àwọn eré orí amóhùmáwòrán-máwòrán Family Family (gẹ́gẹ́ bí Freida) (TV series)Clinic matters (gẹ́gẹ́ bí nọ́ọ̀sì Abigail)taste of Loveàwọn àṣàyàn eré rẹ̀Ibi Poter the Next door wọléoríṣìíríṣìí room (2013) Play's Paradise Deal (2014) couple of days (2016) The In-Laws (2016)a lot like Love (2018)ju (2019) Iroko rẹ̀ Ìpínlẹ̀ ni ẹ sọ̀rọ̀ sí, ó kọ nípa Integrated Science ní ilé-ẹ̀kọ́ ‘Bí Polytechnic'.Ó ṣe ìgbéyàwό pẹ̀lú ọ̀gágun Franklin, ó sọ̀rọ̀ tí bí àwọn ọmọ tẹ́lẹ̀ kí tó ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 2015.Àwọn ìtọ́kasí ní Ọjọ́ìbí ní 1982àwọn ènìyàn alààyè, film Act From Lago Lone Shu Aludọ́gba ìta- | wikipedia | yo |
Rachel Bkam jẹ́ òṣèré ara orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ònkọ̀wé, olóòtú ètò orí tẹlifíṣọ̀nù, àti alátakò gbigbé ènìyàn fi ṣiṣẹ́.. | wikipedia | yo |
òun ni alákọ́so àti adarí Rayzeds Media Ltd; Olúdásílẹ̀ àti Alákòso ti Nigerian Water ski and Wakeboard Federation (Nww); àti alámọ̀ràn fún Performing musician orí Association (manman) pẹ̀lú African Fashion reception Paris.. | wikipedia | yo |
BAkam jẹ aṣoju fún àwọn arìnrìnàjò ati ìgbé ayé alafia.. | wikipedia | yo |
Bkam ti fìgbàkan jẹ ọmọ ẹgbẹ nibi eto iṣakoso ti Amẹrika kan fun awọn alejo kariaye.. | wikipedia | yo |
Ó ma ń ṣe olóòtú ètò Trends & Rachel, ìfihàn tẹlifíṣọ̀nù kan tí ó gbajúmọ̀, tí ó ma n jẹ́ gbígbé sórí afẹ́fẹ́ ní ìkànnì tẹlifíṣọ̀nù NTA, AIT, DSTV, àti Startimes.. | wikipedia | yo |
O tun ṣe agbejade ati agbekalẹ eto “Rachel The Piper” ati ẹya Hausa rẹ “Rachel Mai kakaaki”; eto Telifisonu ti ere idaraya ṣugbọn ti o tun wa fun Iferan ọmọ eniyan.igbẹ aye ibẹrẹ ati ẹkọ rẹ bakam leni taa bi to si dagba ni Ipinle Kaduna sọ́wọ́ awọn obi rẹ, nibiti o ti ni ile-iwe alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, ile-iwe girama, ati ile-ẹkọ giga.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ ede Gẹẹsi ati ere miran ni Ahmadu Bello University ati ṣiṣe fiimu ori ero ni New York Film Academy.. | wikipedia | yo |
Ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́, àkọ́kọ́ ní ilé-Ìgbìmọ̀ àwọn ìtajà ńlá kan, lẹ́yìn náà ní ilé ìsẹbá orin àti sinimá tó sì padà wá kó ipa asíwájú nínú eré Hausa àtigbàdégbà kan tí a mọ̀ ní Ra-iṣẹ́-iṣẹ́ ó ṣe iṣẹ́ Agùnbánirọ̀ rẹ̀ ní ilé iṣẹ́ Nigerian Television Authority International, níbití ó ti ṣe àgbéjáde àti àgbékalẹ̀ àwọn oríṣiríṣi ètò tó bíi Trends, Saturday Morning, and Style Code.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ ṣíṣe Fíímù orí Èrò ní New York Film Academy, lẹ́yìn náà ló ṣètò ìdásílẹ̀ Rayzed Media Ltd.. | wikipedia | yo |
Bkam ṣokùn fa ṣiṣẹ́ eré ìdárayá orí omi ní Nàìjíríà.Ó jẹ́ alámọ̀ràn fún African Fashion reception Paris.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn àrùnile ìjásó.. | wikipedia | yo |
Anna ẹbíeré Banna (tí a bí ní 18 Oṣù Kekee 1995) jẹ́ olúborí ìdíje ẹwà àti òṣèré.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013, wọn dé ládé ọmọbinrin tó rẹwà jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì sojú Nàìjíríà níbi ìdíje ẹwà àgbáyé ní ọdún 2013 bákan náà.. | wikipedia | yo |
O ri yiyan fun ipo oluranlowo pataki si Gomina Henry sókè lori Asa ati Irinrin-ajo, nipasẹ ijọba rẹ gẹgẹ bi ọmọbinrin to rewa julọ ni Naijiria ni ọdun 2012.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2014, o ṣe iṣafihan ere Ak|oko rẹ ninu Super Story.Awọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ebet Bassey je osere omo orile-ede Naijiria ati Amerika ti a yan fun ami-eye Africa Movie Academy Award kan fun ti osere ti o dara julo ni ipa atileyin nipasẹ ipa ti o ko gege bi "Maa dédé" ninu ties that Bind ni odun 2011.Iṣẹ Bassey ti kopa ninu ọpọlọpọ awon fiimu ile Naijiria ati ti Amerika, lara won ni Doctor Bello, Mother of George, NYPD Blue, ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ó ti rí yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó dára jùlọ látàrí ipa rẹ̀ nínu eré ties that dd.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó kéde rẹ̀ wípé òun fẹ́ gbé eré agbọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Saving Father, léte àti La àwọn ènìyàn lọ́yẹ̀ nípa ó àti gbígbé ayé pẹ̀lú kòkòrò àrùn AIDS.. | wikipedia | yo |
Nibi ayeye Nigeria Entertainment Awards ti ọdún 2013, wọ́n tún yan Bassey gẹ́gẹ́ bi òṣèré tó n ṣe àtìlẹyìn tó dára jùlọ ninu fíìmù.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012 bákan náà, Bassey kópa nínu fíìmù Elijìyà Point.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà sì gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ Nollywood and African Film Critics Awards, èyí tí ó wáyé ní Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó kó ipa "Imánì" nínu fíìmù tomorrow Ever After, ó sì ní àwọn Èsì àtúnyẹ̀wò rere fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù náà.. | wikipedia | yo |
Bassey pelu Richard Mofe-Damijo ni won jo ṣeto ayeye Nigeria Entertainment Awards ti ọdun 2016 ni ile-iṣẹ to wa fun ere sise, ile-iṣẹ BMC Tribeca Performing Arts Center ni Ilu New York.Ìgbé ayé rẹ̀ a bi Bassey ni orile-ede Amerika, ṣugbọn o lo awon igba ọdọ rẹ ni ilu Calabar ṣaaju ki o to pada si orile-ede Amerika lati maa gbe nibẹ.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe igbeyawo pẹlu Mark Manczuk.Àwọn itọkasiàwọn Ìtàkùn ìjásóde Official website.. | wikipedia | yo |
Elizabeth Benson (ti a bi ni osu Kẹẹ̀rin Ọjọ 5 Ọdun 1966) jẹ oṣere ara orilẹ-ede Naijiria, O si tun jẹ oninurere Ẹda.ibẹrẹ Aye ati ẹkọ rẹ Benson bẹrẹ iṣẹ osere sise nigbati o wa lọmọdé lomo ọdun marun-un.iṣẹ-iṣẹ rẹaṣeyọri rẹ ati fifi iṣe fiimu silẹ Benson di gbajumọ oṣere nigbati o ṣe ifihan ninu Fortunes, ere Telifisonu kan ti agbejade rẹ waye ni ọdun 1993.. | wikipedia | yo |
Benson ko ipa ti Iyaafin Agnes Johnson ninu ere naa, eyiti o waye fun bi ọdun meji lori ikanni Nigerian Television Authority.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1994, ipa rẹ̀ nínu Glamour girls, sinimá àgbéléwò biribiri kan tí ó dá lóri ópò jẹ́ agbọ̀n ìṣèlà tó wáyé nínú ayé rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà sọ di olókìkí ó sì fa kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olólùfẹ́ fíìmù Nàìjíríà fẹ́ràn rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ọpọlọpọ ri bi ọkan ninu awọn Iyaafin akoko ti Nollywood.. | wikipedia | yo |
Ni iyalẹnu, ni kete ti iyi rẹ bii asiwaju oṣere bẹrẹ si lekun paapaa ju bi a ti ṣe lero lọ, lojiji naa ni Benson fi iṣe osere silẹ ni ọdun 1996.ipadabọ rẹ si Nollywood latigba ti o ti pada si Nollywood, a gbọ pe o ti di iyipada onigbagbọ to si n ṣe waasu Ihinrere lemọ́lemọ̀.. | wikipedia | yo |
Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan, o ṣalaye pe oun yoo ṣiṣẹ nikan ninu awọn fiimu ti o gbagbo wipe o wa ni ibamu pẹlu igbagbọ rẹ.Igbe aye rẹ Benson padanu ọkọ akọkọ rẹ (Samuel Gabriel Etim) ni akoko ti o wa ni aarin awọn ọdun 20 rẹ.. | wikipedia | yo |
O royin wipe iwa oko oun je ki oun ni anfani lati le tẹsiwaju pẹlu mimomójútó awon omo re lehin pipadanu naa.aṣayan awon ere re ninu awon ipa re ti o gbajumọ julọ ni ipa rẹ bi Tituti ninu ere Femi Osofisan kan, Moroúntòdun ati Iyaafin Agnes Johnson ninu Fortunes, ere Telifisonu kan ti o waye fun bi ọdun meji lori ikanni Telifisonu ti Naijiria (NTA).. | wikipedia | yo |
O kopa ninu ọpọlọpọ ere agbelewo Nollywood bii Evil men 1 and 2, Shame, conspiracy, Izaga, burden, Stolen Child, Faces, Dead End, Tyapáku, Glamour girls, Body of vengeance ati ogunlọgọ awọn fiimu miran.Awon itọkasiawọn ita ìjásóde Liz Benson on Her New Life at 40 Liz Benson's Profile on fimvillage.. | wikipedia | yo |
Caroline Chifoto je osere ara orile-ede Naijiria ati biritísì, to gbajumo fun kiko awon ipa bii Sasha Williams ninu ere as if, Elaine hardy ninu ere footbaStade' Wives ati ipa Orthowoman ninu torchwọodibere aye re a bi Chihias ni England si awon obi omo orile-ede Naijiria ti won je elédè Igbo.. | wikipedia | yo |
ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlá, wọ́n rán Chifoto lọ sí ilé-ìwé Bodini ní Nàìjíríà ní ìgbìyànjú láti jẹ́ ki ó kọ àwọn ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ láti di òṣèré sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ṣaaju eyi, o ti maa n lọ si awọn idanileko ni ipari gbogbo ọsẹ ni Ilu Italia Conti.. | wikipedia | yo |
Lakoko ti o pada si United Kingdom, o forukọsilẹ ni Brunel University nibi ti o ti keẹkọ ìsọgun iwosan sugbon o fi ile-iwe silẹ lai gboye.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa o ri anfani sikojìyà si Academy of Live and Recorded Arts ti Ilu UK.kíkópa re ninu ere telifisonu lehin awon ipa re ninu Holby City, casualty, ati fiimu BabyMother to gba ami-eye, Chihias ri akoko ipa re to se saananan bii Sasha Williams ninu as if ni odun 2001.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó di ọdún 2004, ó rí ipa míràn bí Elaine hardy, ọ̀rẹ́bìnrin Kyle pascoẹ nínú eré footbáller's Wives.. | wikipedia | yo |
Lara awon ise telifisonu re miran ni 40, Judas Kiss, free Fall ati brothers and Sis.O kopa bii Lisa Hallett, omo egbe òkunkun kan ti o ti yipada si apakan eniyan, apakan ere ninu "ìkọ̀sẹ̀àbùmọ́", o si tun kopa gege bi Tamara, Adede àlùrokonu kan ninu ere supernatural.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, ó tún kópa gẹ́gẹ́ bi Queen Tamlin nínú Shannara Chronicles.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ ló dé kópa gẹ́gẹ́ bí Angela Omìíràn nínu eré ẹ̀kínísí aláṣeyọrí kan ti EbonyLife "the Governor." rẹ̀ nínu sinimá àgbéléwò gẹ́gẹ́bí òṣèré fiimu, ChiỌpẹ́nkan ti kópa nínú fíìmú eragon.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kanyisilẹ mbau(bii ni ojo kẹẹdọgbọn osu kẹwàá odun 1986) je osere ati atọkun eto lori telefisonu ni orile ede South Afrika.. | wikipedia | yo |
M̀báú di gbajúmọ̀ nítorí ipa dọbsie tí ó kó nínú eré Muvfọwọ́ ní ọdún 2004.. | wikipedia | yo |
O ṣe atọ́kùn fún ètò The Scoop ati The Big Secret.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ ayé rẹ wọ́n bi Khanyà ní ọdún 1995.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀, Lynette sisí mbau ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ ti Barclay Bank.. | wikipedia | yo |
Iya rẹ ati baba rẹ ko ti ṣe igbeyawo nigba ti wọn fi bi Khanyasilẹ, baba rẹ ko gba a gege bi omo re, sugbon o se ìsọmọlórúkọ fun.Iṣẹ ni ọdun 2004, won fi mbau rọpo Lindìwé Chibi lati kó ipa DORSi ninu ere Muvfìtara.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ọdún kan, wọ́n lè kúrò nítorí pé ó ti fẹ́ràn àríyá jù.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó ṣe adájọ́ fún ètò keji ti turn it out, èyí tí ṢauluBC gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye gege bi osere to dara ju lo fun ipa ti o ko ninu ere Red Room lati odo South Africa International Film Academy Awards ni ọdun 2019.Àṣàyàn àwọn eré ti o ti ṣeàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Hlubi Mboya (Bii ni ojo keji osu keta odun 1978), je osere ni orile ede South Afrika... | wikipedia | yo |
O si farahan ninu ere Dora's Peace ni ọdun 2016, eyi si lo je ko gba ami eye Best Supporting Actress lati Odò SaFTA Award.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye Best Supporting Actress lati ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ eto V-Entertainment ni ọdun 2013.aṣayan àwọn ere ti o ti ṣeawọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Boitumelo Thulo (Bii ni ojo kejidinlọgbọn osu kerin odun 1990) ti oruko inagi re je Boboty je osere, olorin, onisowo ati modeli lórílẹ̀ ede South Afrika.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ Aye re won bi Thulo si ilu Potchefstroom, ìyá Mama re si lo to dagba.. | wikipedia | yo |
Oun nikan ni omo iya re bi.O lo si ile eko giga ti Monyash University nibi ti o ti ko eko psychology and Criminology, sugbon ko pari eko re nitori pe ko ri owo ile eko na san.ise Thulo bere si ni se atọ́kùn eto pelu Crib note ni odun 2011.. | wikipedia | yo |
Oun ati Stevie French jọ ṣe atọ́kùn fun eto the media career Guide Show lori JeBC.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe atọ́kùn fún orísirísi ẹ̀tọ́ bíi Skyroom live, Ésomeric Africa, Club 808, Zoned, Change Down, àti Big Brother Africa.Ni ọdún 2012, ó kópa nínú eré Rock Ville.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2014, o farahan gege bii Betty ninu ere Dear Betty.. | wikipedia | yo |
O ko ipa ránpẹ́ ninu ere Mrs right Guy ni odun 2016.Thkin koko farahan gẹ́gẹ́ bi olorin nibi ayẹyẹ Migos culture tour ni ọjọ kokanlelogun osu kẹwàá odun 2017.. | wikipedia | yo |
Ni ojo ogbon osu kejo odun 2018, o gbe orin ti o pe akole re ni wúz Olaini, orin naa si gba ami eye Best Collabo lati ọdọ South African hip-hop Awards ni odun 2018.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kejo osu keji odun 2019, o gbe orin re keji jade ti akori re je Bakae.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
thando Thabethe (Bii ni ọjọ kejidinlogun osu kefa ọdun 1990) jẹ oṣere, DJ, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati ambasedo akọkọ lati ile Afrika fun Niopóránṣẹ́.. | wikipedia | yo |
O ṣe atọ́kùn fún ètò thandò báres all lórí Channel TLC.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ iṣẹ ori RAdìíọ ni ọdun 2008 ni Ile iṣẹ UFMFM ki o to pada lọ si Ile iṣẹ YFM ni ọdun 2011.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó ṣe atọ́kùn fún ayẹyẹ South African Music Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, òun náà sì ni ó tún ṣe atọ́kùn fún South African Film and Television Awards.Ní ọdún 2018, ó kó ipa Linda Nopalov nínu eré Housekeepers.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó kó ipa Zhhle Malinga nínu eré Love Lives Here.Ní ọdún 2019, wọ́n yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ atọ́kùn ètò tó dára jù lọ àti ètò ọrọ̀ tó dára jù lọ, ó sì gba àmì ẹ̀yẹ ètò ọrọ̀ tó dára jù lọ.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
ughọ Lotachukwu Jacinta Obianuju Amelia jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti gbogbo eniyan mọ si Lota chukwu .. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn kíkópa rẹ̀ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jenifa's Diary ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé, Juliana Okìlọde àti Falz, níbi tí ó ti kó ipa gẹ́gẹ́ bi "Kíl", Ọ̀rẹ́ àti akópa Aṣíwájú, Jenifa .. | wikipedia | yo |
O jẹ ẹnìkan to nifẹ si ere idaraya yoga.ibẹrẹ aye rẹ Lota ni a bi ni Nsukka, Ipinle Enugu, Naijiria ṣugbọn o ṣe igba ewe rẹ ni Ilu Benin.. | wikipedia | yo |
Lota ni ọmọ ikẹhin ninu awọn ọmọ mẹrin ti awọn obi rẹ.. | wikipedia | yo |
O keeko imo itẹsiwaju iṣẹ ogbin ni Ile-ẹkọ giga ti Benin.. | wikipedia | yo |
Lẹsẹkẹsẹ tó parí ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Benin náà ló tún lọ kéẹ̀kọ́ eré ìtàgé ṣíṣe ní Royal Arts Academy tó wà ní ìlú Èkó, Nàìjíríà.Iṣẹ́ iṣẹ́ ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré, Lota jẹ́ afẹwaṣiṣẹ, ó sì ti kópa ninu ìdíje ẹwà ti Nàìjíríà ní ọdún 2011 lẹni tó ń sojú ìpínlẹ̀ Yobe.. | wikipedia | yo |
ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe rẹ̀ ní ọdún 2011 ṣùgbọ́n ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn tí ó hàn nínú Jenifa's Diary níbití ó ti kó ipa "Kíkiki.. | wikipedia | yo |
O tun ti kopa ninu awọn ere agbelewo bii Royal Hibis Hotel, Falling, Fine Girl, The Arbitration, Dognapped ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Lota ko ipa asiwaju ninu fidio Reminisce kan, Ponmile ati ninu fidio Aramide, Why So Serious.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017 ó kéde ṣíṣe ìfihàn tẹlifíṣọ̀nù kan tí ó pè ní "Lota Takes" | wikipedia | yo |
Ìfihàn náà dá lórí bí a ṣe ń dánó oúnjẹ àti bí a ṣe ń gbé ìgbésí ayé, èyítí ń júwe lọ̀tá gẹ́gẹ́ bí olólùfẹ́ oúnjẹ àti ìṣẹ̀dá.. | wikipedia | yo |
Ìfihàn náà ti rí yísì ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn gbajúmọ̀ ìlú Nàìjíríà tó fi mọ́ Adekunle Gold, Tosin Ajibade, Aramide, àti Mc Galaxyàwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn aláàyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1989.. | wikipedia | yo |
Sylvesterine strike jẹ́ òṣèré, akọ̀wé àti adarí eré orí ìtàgé lórílẹ̀ èdè South Áfríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé rẹ̀ Wọ́n bí sí ìlú Pretoria.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Cape Town, ó sì gboyè nínú ìmọ̀ máa ní ọdún 1993.Iṣẹ́ Strike jẹ́ adarí fún àwọn òsèré ní ilé iṣẹ́ Fortune Cookie Theater.. | wikipedia | yo |
O ti dari àwọn eré bíi miser (2012), Tartuf (2017), Tobacco and the harmful effect thereof (2016).. | wikipedia | yo |
Láàárín àwọn iṣẹ́ tí Strike ti darí ní Miss Dietrich Retagts (2015), Dop (2019), àti EClíd (2019)... | wikipedia | yo |
O ti kopa ninu awon ere bii Those Who Can't, Black Sakúlẹ̀kúlẹ̀, D dogs, ati The Hot Zone.Awon ami eye ti o ti gba o gba ami eye adari tuntun ti o dara ju lo lati ọdọ Rosalie van den Gucht ni odun 2004.. | wikipedia | yo |