cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queenstown Girl's High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Pretoria níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Aya.Iṣẹ́ Mfenroro di gbajúmọ̀ ní ọdún 2011 fún ipa NoLunda Memela tí ó kó nínu eré Generations èyí tí Mfún Vundak gbé jáde.Ní Oṣù Kìíní Ọdún 2015, ó kó ipa Reba nínu eré Ashes to Ashes pẹ̀lú àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi Tina Jaxa àti Menzi Ngubane.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kejì, Ọdún 2017, ó kó ipa tíbo àatza nínú eré The Queen.àṣàyàn àwọn eré àkò Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Nkhenṣánì mangan jẹ́ òṣèré àti aránsọ ní orílẹ̀-èdè South Africa.Iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2000, Manganyi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ aránṣọ tirẹ̀ tí ó pè ní Stoned Cherrie.. | wikipedia | yo |
Ìkan lára àwọn aṣọ tí ó rán gbayi láti ilé iṣẹ́ ìròyìn drum.Ilé iṣẹ́ náà ma ń ṣe gíláàsì fún ojú.. | wikipedia | yo |
Diẹ ninu awọn iṣe rẹ si wa ni Fashion Institute of Technology nibi ti won ti se ifihan rẹ nibi ayẹyẹ Black Fashion Designers ni ọdun 2016.mangan ti kopa ninu awọn ere bii Legend of the Hidd City, Tarzan, The Epic Adventures ati kickbox 5 ati bẹẹ bẹẹ lọ.Ni ọdun 2003, o se adajọ fun eto Pop Star ti wọn se lórílẹ̀ ede South Africa.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Funmi Martins ti won bi ni ilu Ileṣa ni Ipinle Osun ni inu osu Kesan an odun 1963 je osere ori-itage ati sinima agbelewo omo orile-ede Naijiria.ibẹrẹ aye ati Eko Kiku bi Funmi ni IpinleOsun Osun ni inu osu Kesan an odun 1963, o lo si ile-eko alakoobere oke-ona ati ile-eko girama ni ipinle ilu Abeokuta ni ipinle Ogun.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ girama, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní bẹ́ẹ̀pọ̀ Jordanitatìtì Institute ní ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gba ìwé-ẹ̀rí dípúlọ́mà nínú ìmọ̀ Jordanijìnjinte.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèréfunmi kọ́kọ́ ṣe Modeling fúngbà díẹ̀ ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ eré iṣẹ́ eré orí-ìtàgé.. | wikipedia | yo |
O di ilu-mooka látara ere kan ti Ogbeni Fidelis Duker gbe jade ni odun 1993.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínu àwọn eré ọlọkan-o-kan ni orile-ede Naijiria ni asiko odun kẹfà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí igbeyawo òun ati ọkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ forí sopọn ni ó tún fẹ́ gbajú-gbajà olórin Afro Jùjú tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí sir Shina Peters tí ó sì bímọ ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bíbíbí Alọ́rọ̀pọ̀ Peters ní ọdún 2002.IKÚ rẹ̀ papọ̀ da ní ọmọ ọdún méjìdínlógójì nkan bí oṣù méjì lẹ́yìn tí ó bímọ rẹ̀ tan látàrí àìsàn ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Ó kú sí ilé ìwòsàn kan ní agbègbè Agege ní ọjọ́ karùn-ún Oṣù karùn-ún Ọdún 2002.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa Thuli nínú eré Gaz'lam (2002–2005), èyí sì ló jẹ́ kí wọ́n yàán fún òṣèré gébìnrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ ROòró ROkò Awards.. | wikipedia | yo |
Zainab Bukky Ajayi (2 Oṣù Keèjì 1934 6 Oṣù Keèje 2016) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbé ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ Bukky Àjàyí ni a bí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n ó parí ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè England, United Kingdom pẹ̀lú àtìlẹ́yìn sikolashipu Ìjọba Àpapọ̀ kan.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1965, ó kúrò ní England wá sí Nàìjíríà níbití iṣẹ́ rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi oníròyìn fún Nigerian Television Authority ní ọdún 1966.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù "Village Headmaster" ní àwọn ọdún '70s ṣaájú kí ó tó lọ kópa ToCheckmate, eré tẹlifíṣọ̀nù Nàìjíríà kan tí wọ́n gbé síta ní àkókò ìyìn àwọn ọdún 1980 sí ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1990 ní àkókò iṣẹ́ eré eré rẹ̀, ó ṣe ìfihàn nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó pẹ̀lú Critical assignment, Diamond Ring, witches láàrin àwọn míràn.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, àwọn ìlọ́wọ́sí rẹ̀ sí iṣẹ́ fíìmù ti Nàìjíríà ṣokùn fa n tí wọ́n fi fún òun àti Sadiq dábá ní ẹ̀bùn Industry Merit Award níbi ayẹyẹ 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards.Àkójọ eré Reiku rẹ̀ Ajayi kú ní ibùgbé rẹ̀ ní Surulere, Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ 6, Oṣù Keèje Ọdún 2016 ní ọmọ ọdún 82.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Fisáyọ̀ Ajisola , ti a tun mọ ni FreeZon, jẹ oṣere tẹlifisiọnu ati oṣere fiimu, awoṣe ati akọrin.. | wikipedia | yo |
Oruko re tan daada julo fun ipa re ninu ere tẹlifisiọnu Naijiria kan Jenifa's Diary, pelu ajọṣepọ Funke Akindele.. | wikipedia | yo |
Oruko re tun tan fun awon ipa re ninu awon ere tẹlifisiọnu; this life, Netitar, Shadows, Burning spear, Circle of interest ati The Story of Us .. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ akẹ́kọ gboyè ní Biàyànfẹ́sitiri láti Federal University of Agriculture, Abeokuta (FUNAAB), Ìpínlẹ̀ Ògùn.Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ fisáyọ̀ ni a bí ní Èkó, Nàìjíríà àti pé ó jẹ́ ọmọ ìkẹhìn nínú àwọn ọmọ mẹ́rin ti àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ elédè Yorùbá, ó sì wà láti Ahabu ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ajipẹpẹ bẹ̀rẹ̀ sí kópa nínú àwọn eré àti àwọn eré Oniwà, làkókò tí ó wà ní ilé-ìwé Àko mẹwa Federal Federal Government College (FG) Odogbolu, Ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Keje Ọdún 2010, ó forúkọsílẹ̀ ní ilé-ìwé Peftì tó wà fún eré ìtàgé tí Wale Ajípàdé dá sílẹ̀ ní ìlú Èkó, Nàìjíríà, níbi tí ó ti kẹkọ eré ìtàgé.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ akiyesi akọkọ rẹ, waye n bi nnena and Friends Show, ni Oṣu Kẹwa Ọjọ 1, Ọdun 2010, nibiti o ti ṣe agbekale iṣẹ orin kan.. | wikipedia | yo |
Lakoko ti o wa ni Ile-ẹkọ giga, Ajisola ṣeto ipilẹ kan ti kii ṣe ti ijọba (NGO) Jewel Empowerment Foundation, pẹlu emi ise lati mu wahala ti awujo duro nipa sise ifiagbara fun awon odo ati àìja awon ọmọde.Iṣẹ Iṣẹ fisáyọ̀ bẹrẹ iṣẹ osere rẹ ni odun 2011, pẹlu awon ipa ninu awon ere tẹlifisiọnu Naijiria bii “Tinsel", “spear Kowe" ati "Circle of interest" | wikipedia | yo |
O gba isinmi kuro nibi ere sise ni osu Kesan, odun 2011 nigbati o ri ìgbáwọlẹ̀ si ile-eko giga.. | wikipedia | yo |
Ajipẹpẹ ṣe ifilọlẹ iṣẹ́ ṣíṣe fiimu rẹ ni ọdun 2016 pẹlu ṣiṣe fiimu Road to Oruin ni ifowosowopo pẹlu ipilẹ rẹ, Jewel Empowerment Foundation (Jef) pẹlu ero lati gba ijoba níyànjú lati gbe igbese fun ipese awon ise fun awon odo Naijiria.. | wikipedia | yo |
Aremu Afolayan jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún Òṣèrékurìn Kúnlé Afọláyan, tí ó jẹ́ òṣèré àti adarí eré tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ adarí eré tó peregedé jùlọ.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀Aremu Afọláyan jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà adarí eré àti olùgbéré-jáde Adé Love tí ó jẹ́ ọmọ ìlú Ìgbómìnà ní ìpínlẹ̀ Kwara.. | wikipedia | yo |
Kunle di.Ìlú-mooka latari ere rẹ̀ kam ti o gbe jade ti o pe ni idamu àkọtọ́ ni odun 2009.Igbe aye ReAremu fe Aya re Arabinrin KaFilayi Olayinka Quka, ti won si bimo obinrin kan iyùnade Afolayan.Ami Ẹyẹawon itọkameric Mamale Film Actorṣàwọn Eniyan Aapadara of Birth Missing (Living People)Place of Birth Missing (Living People)Yorùbá Mamale Actorrin Actors from from Lagos Actors in Yoruba Cinéma.. | wikipedia | yo |
àfẹ́ẹ̀fẹ́z Abiodun ti gbogbo eniyan mo si jẹ oṣere ori-itage ati sinima, olùgbéré-jade ati adari ere Yoruba ọmọ orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fún ní ìnagijẹ rẹ̀ òwò látàrí bí ó ṣe jẹ́ Olówó-Orm àti Ọ̀rẹ́ tímọ́ tímọ́ gbaju-gbajà òṣèré Ori-ìtàgé kan Yemi Oja Obò ayé àti ètò ẹ̀kọ́ kòlé bí àfẹ́zz ní ìlú Àyìn ní ìpínlẹ̀ Oyo.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé- ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ti St.. | wikipedia | yo |
Paul ni ilu Aroko ni Ipinle Ogun, o si tun lo si ile-eko girama Faramo ni Ipinle Oyo.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀, ó lọ sí ìlú Èkó láti wá bí ìgbé ayé yóò ṣe rọrùn ní àsìkò ọdún 1980.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèréàfẹ́àfẹ́z ti bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe eré-ìtàgé láti lásìkò tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama nígbà tí ó kọ eré kan tí ó pè ní kọ́kọ́rọ́ ayé, tí àwọn olùkọ́ àti akẹgbẹ́ rẹ̀ sì gbóríyìn fún fún iṣẹ́ ọpọlọ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
fẹ́b dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré ní ilẹ̀ Nàìjíríà pẹ̀lú ìrànwọ́ Razaq Ọláyíwọlá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ọjọ́pọ̀gì.. | wikipedia | yo |
Bukola Adeẹyọ jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde, adarí ère àti aṣojú fún ilé iṣẹ́ kan ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti Èkó rẹ̀wọ́n bi Bùkọ́lá ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1989 ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ní ìpínlẹ̀ ogun.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-Níṣe ti Moshood Abiola ( MaiPoly) ní ìlú Abeokuta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.Iṣẹ́ Rets bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe eré ìtàgé ní ọdún 2008, lẹ́yìn tí ó dára pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ ìyìn jáde Odunlade Adekola.. | wikipedia | yo |
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré ilé owó.. | wikipedia | yo |
Ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ìgbé ayé Rebuilding Adeẹyọ jẹ́ aya ọ̀gbẹ́ni Bello Oladipo tẹ́júyin tí ó jẹ́ adarí àti òṣèré orí-ìtàgé.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí ọmọ obìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Janell.. | wikipedia | yo |
O tun bimo miiran fun enikan ti won pe ni LASben.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
rẹmi Abiola ti wọ́n bí ní oṣù Kẹwàá ọdún 1953 tí ó jáde láyé ni oṣù keje ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, àti adarí eré sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O jẹ iyawo Moshood Abiola.rẹmi papo da ni ojo kokandinlogbon osu kejo odun 2009, latari aisan jẹjẹrẹ ti jakun emi re.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọmọ méjì ni ó gbẹ̀yìn olóògbé náà.Iṣẹ́ reremi kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣe ni Fielding School for Dramatic Arts ní ìlú England ní àsìkò ọdún 1970s, lẹ́yìn tí ó fìṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Onbánisọ̀rọ̀ ní Ilé-iṣẹ́ ''Nigeria Airways.. | wikipedia | yo |
Hassan Taiwo Akinwándé, tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìlélógún Oṣù Kejì Ọdún 1960, tí a mọ̀ sí Stage Name Rets, jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí ó ti kópa nínu eré àti Fitanma oríṣiri.Iṣẹ́ rẹ̀Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ní ọdún 1980 nígbà tí ó kópa nínu eré onípele ti ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ fèyí kọ́gbọ́n.. | wikipedia | yo |
Ìròyìn gbé wípé wọ́n fi ẹ̀sùn ìgbé egbògi olóró kàn án ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
Aas-wúyẹ́ yí túbọ̀ mú kí òkìkí rẹ̀ tún kàn síwájú sí.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn òṣèré tí wọ́n jọ wà ní sáwawu ni Taiwo Hassan, ẹ̀bùn Olóyèdé Ola-Ìyà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe, Yinka Quka àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí-Century Nigerian Actresses of Birth Missing (Living People)àwọn Ènìyàn Alààyè AlààyèYorùbá ActET6].[ in Yorùbá Cinéma.. | wikipedia | yo |
Bose Àlàó Omotoyọsi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà Oṣù Kíní Ọdún 1985, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùdarí eré, ,àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi Bọ́sẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó sì jẹ́ àbílé Kẹrin nínú ẹbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Command àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ti ti Gedions Compréhwn High School ní ọdún 2002... | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú ní inú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní inú ogbà Yunifásítì ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó kọ́ ẹ̀kọ́ ní bíbí, amo ó fagilé ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ níbẹ̀ lẹ́yìn látàrí tí ó ṣe ètò ìwá-n- mọ́ ọ, tí sí bí àwọn ọmọ rẹ̀ tí kò sì lè padà sẹ́nu ẹ̀kọ́ rẹ̀ mọ́.. | wikipedia | yo |
O lo si ile-eko Lagos srate city Polytechnic ni Ikeja ni ipinle Eko, ti o si gba iwe eri eri ninu imo AD.S.Iṣẹ Reminitara rẹ bi osere je okan ninu awon osere Nollywood, olùgbéré, olùgbéré-jade to dáńtọ́ .O di ilu-mooka odi re ti o ko ninu ere Coòmìniraigbe Re’’ Reyìì se igbeyawo pelu Ogbeni onisowo kan ti oruko re n je Razak ti won si won si bi omo obinrin meji funra won.Awon aṣayanere Salav) ika(2006) Abo-2007) Mo-FM2013) Between (2014) Day(2016) ere ti ere ti o ti gbe jade Awards Kingdom Kingdom (Best Actress) Awon aṣayan ere ree tun wo awon osere bii itan okeỌ̀gbẹ́ni Akindele Ibrahime Isong Ekeinde Ekeinde Ekeinde tun wo list of Nigerian Nigerian Film producer producer Actress Actress September Alao jẹjẹrẹ ẹgbẹ̀rún ẹgbẹ̀rún New photos, Retrieved 12 October 2016 Nollywood Actress September Itamari win baby 4th Baby, Retrieved 12 of wife Actress of wife of foot lákòókò rírán opó lákòókò first first abúlé deal, Retrieved 12 to 2016 my by ke ilu bùkún Nu- Bose G- Good Àlàó, Retrieved 12 (Awon 2016 ni Ọjọ́ìbí & Film Act (mànàmáná & Nigeria alààyẹ̀ Maria Ogungi C-Béèrè Nigerian Act Act In Yoruba Yoruba Yoruba Cines from Lagos .[4.. | wikipedia | yo |
O gba ẹbun Africa Magic kan fun ipa rẹ ninu aṣamudọgba fiimu Dazzling Mirage Aye Akìlọ BI Akindoju ní Ọjọ́ 8 Oṣù kèéta Ọdún 1987 ní ìdílé àwọn ọmọ mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
O lọ ile-iwe girama ti Queen's College, Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti o gba iwe-ẹri ti idanwo West African Examinations Council (WAEC), o tẹsiwaju lati keeko nipa Insurance ni Ile-ẹkọ giga Yunifasiti Eko.. | wikipedia | yo |
Ó tún gba oyè gíga láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Pan-Atlantic, níbi tí ó ti kẹ́ẹ̀kọ́ Media àti Communication.Iṣẹ́-iṣẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2005 láti orí ìpele ṣááju kí ó tó lọ sínú àwọn sinimá àgbéléwò.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ Alan Poza (With OC ? Dazzling Mirage The CEO CEO Fifty Aŕn l'eré Ẹ̀bùn àti ÌFISỌRÍ rẹ̀ The Future Awards - 2010 Actor of the Year2016 Africa Magic Viewers Choice Awards - Travzer Awarddébi Africa Movie Academy Awards - Most Promising Actoking Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ogun abẹ́lé jẹ́ ogun láàárín àwọn ẹgbẹ́ tó ṣètò láàárín ìpínlẹ̀ kan náà (tàbí orílẹ̀-èdè ).. | wikipedia | yo |
Èrò ti ẹgbẹ́ kan lè jẹ̀ẹ́ lati gba ìṣàkóso orílẹ̀-èdè tàbi agbègbè kan, lati gba ominira fún agbègbè kan, tàbi lati yi àwọn ètò imulo Ijọba padà.. | wikipedia | yo |
ọ̀rọ̀ náà jẹ́ Calque ti Latin Bellum Cidepo èyí tí a lo láti tọ́ka sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ogun abẹ́lé ti Roman Republic ní ọ̀rúndún 1st BC.Púpọ̀ julọ àwọn ogun abẹ́lé òde òní pẹ̀lú ìdásí nipasẹ àwọn agbara tí ó wá láti Ibi-Onimíràn.. | wikipedia | yo |
Regan ninu iwe rẹ Civil wars and foreign powers (2000) nipa ida meji ninu meta ti àwọn 138 intraState rògbòdìyàn láàárín World War II eyi tí ó ti ń ṣúmọn ìparí rè ati 2000 rí Ọ̀kẹ́rẹ́ Interàkàwé.. | wikipedia | yo |
Ogun abẹ́lé jẹ́ rògbòdìyàn-kíkankíkan kan, nígbàgbogbo pẹ̀lú àwọn ológun ológun, èyí tí ó dúró,tí ó ṣètò àti tí ó wà ní ìwọ̀n-nlá.. | wikipedia | yo |
Àwọn ogun abẹ́lé le è jà sí ọpọlọpọ àwọn olufaragba ati lílo àwọn orísun pataki.Awò àwọn nkan ti ìwádìí ogun abẹ́lé Lars-Erik Cederman, Manuel Vghot.. | wikipedia | yo |
"Dynamics àti ẹ̀ṣẹ́cs ti ogun abẹ́lé.” Ìwé àkọsílẹ̀ ìpinnu rògbòdìyàn Kahenvas Stathis n.. | wikipedia | yo |
"Ogun Abẹ́lé." Oxford Handbook of olùkọ́ni Politics, ṣàtúnkọ́ nípasẹ̀ Bobox Carles, Stokes Susan C., 416-4.. | wikipedia | yo |
Àwọn ìṣọ̀tẹ̀ inú ní Russia, Spain, Greece, Yugoslavia, àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn; Online Patrick M.. | wikipedia | yo |
9, 2003 pp 247+ ẹ̀yà ORÍ ayélujára Archivedàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Esther Ene audu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kẹta ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
She is popularly known for Starring in the films dinner (2016), Mystified (2017) and order of the ring (2013).Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Esther ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta ọdún 2986, sí inú ẹbí òṣìṣẹ́ fẹ́yìntì nílé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà kan ọ̀gbẹ́ni James Audu .. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ lo gbogbo aye rẹ ni Ipinle Eko ni inu bárékè ologun tí ó wà ní ìlú Ikeja, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ọmọ bíbí ìlú Ọlámabọ́rọ̀ ní ìpínlẹ̀ kogi ni wón.. | wikipedia | yo |
Esther ni ó jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn ọmọ márùn ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní Ìpínlẹ̀ Èkó àmọ́ òun àti àwọn òbí rẹ̀ kó lọ sí ìlú Àbújá ní ọdún 2002, tí ó sì lọ parí ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
lẹ́yìn ilé-ẹ̀kọ́ girama, ó wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Jóṣ ní ìpínlẹ̀ Plateau láti keko gbàwé ẹ̀rí ní inú ìmọ̀ Business Management ní ọdún 2006 tí ó aì jáde ní ọdún 2010.Iṣẹ́ rẹ̀ Esther bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré orí-ìtàgé ṣiṣẹ́ láti ìgbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama tí ó sì ma ń ṣojú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ níbi eré oníṣe ìta gbangba.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1996, ó wà lára àwọn ójẹ wẹ́wẹ́ tí wọ́n yàn láti.sojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ìdíje kídàmọ́n ní orílẹ̀-èdè Gana.. | wikipedia | yo |
Látàrí èyí, ó di ẹni tí ó nífẹ sí láti máa ṣeré dá àwọn ènìyàn lára yá.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́kọ́ kópa nínu eré UnGodly Romance and Sins of RCHELal in Jos, eré tí Alex mouth kọ.. | wikipedia | yo |
Esther fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eré yí ni ó jẹ́ kí òun lánfàní láti di òṣèré Nollywood loni.. | wikipedia | yo |
Chigozie Stephanie Alichi (ti a bi ni ojo 23 Oṣu kejila ọdun 1993), ti a mo ni Chizzy Alichi, jẹ oṣere fiimu ti Ilu Nàìjíríà.Igbe Aye rẹ Chizzy Alichi wa lati Eedza Nkwubor Nike ni Enugu East, Ijọba Agbegbe kan Naijiria.. | wikipedia | yo |
Iroyin rẹ kan jakejado nigba ti o kọ ile nla fun awọn obi rẹ ni ọdun 2017.. | wikipedia | yo |
O n gbe ni iyawo, Ipinle Delta.Iṣẹ rẹ o darapọ mọ Nollywood ni ọdun 2010 láìrò tẹlẹ .. | wikipedia | yo |
Ó tọrọ fún ààyè láti kópa nínu fíìmù kan, wọ́n sì ṣe àfihàn rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bi òṣèré nínu fíìmù Magic Money ti Mercy Johnson àti Bob-Manuel Udokwu náà kópa nínu rẹ̀.Ìṣẹ̀lẹ̀ gboogi tó ní ipa rere nídìí iṣẹ́ rẹ̀ ní eré Àkàràòkú, tó túmọ̀ sí àkàrà gbígbóná", ní 2016.. | wikipedia | yo |
Ìwé ìpolówó rẹ̀ ló gbalẹ̀ kan lórí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ káàkiri tí àwọn èèyàn fi lérò wí pé alákàrà ni lóòótọ́.. | wikipedia | yo |
Eyi fun ni anfaani lati kopa ninu awon ere miiran si ni ọdun 2017. Ni ere akaraòkú, to tumọ si akara gbígbóná", ni 2016.. | wikipedia | yo |
Eyi fun ni anfaani lati kopa ninu awon ere miiran si ni ọdun 2017..Awon ifarahan re ninu orinawon ẹ̀bùnàwọn aṣayan ere rẹàwọn itọkasiawon Ìtàkùn ìjásóde Chizzy Alichi Official website.. | wikipedia | yo |
Liz AIShat Ailrin (ti a bi Elizabeth AISH Ailrin, orukọ akọkọ ti a ko ni ọna miiran si jẹ Lizzy) jẹ oṣere ara ilu Naijiria kan eniti o se ẹya pupo julọ ni ile-iṣẹ fiimu ti Yoruba.. | wikipedia | yo |
O ti gba ami "eye osere ti o dara julo" ni ti ebun awon odo awon aseyori ni odun 2012, awon "Eniyan ilu fun ami eye ebun fiimu fun eniyan fiimu Yoruba ti odun" ni awon ere Idanilaraya Ilu eniyan ni odun 2014, "Ààmì Eye idanimo pàtàkì Ilu Eniyan ni ilu" awon ebun idanilaraya Ilu Ilu ni odun 2017 ati ebun "eye Ilu Fiimu Eniyan fun ti fiimu Yoruba ti odun (obinrin)" ni awon ere idaraya Ilu eniyan fun ti akoko elekeji ni odun 2017.Ìgbésí ayé ati Eko Alágbárarinrin ngbe ni Ipinle Eko, Agbegbe iha guusu iwo orile ti Naijiria eyiti o je eyiti awon eniyan Yoruba ti Naijiria tedo pupo julo julo.. | wikipedia | yo |
Ailrinrin se apejuwe ninu ìjomitoro pẹlu the Punch that at a tender age she had begún Hawking edibles pelu iya re ni igboro Naijiria lati ri owo fun jo'gun ngbe aye.. | wikipedia | yo |
Ailrinrin pari ẹkọ ile-iwe alakọbẹrẹ ati Ile-iwe giga o si Jere re "iwe-ẹri ile-iwe ńkọ́kọ́ silẹ” "ati “iwe-ẹri ile-iwe giga ti Iwọ-oorun Afirika” lẹsẹsẹ.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gba Adélọ́rìnrìn ní ilé ìwé gíga Adékúnlé Ajasin Yunifásítì ní ìpínlẹ̀ Òndó láti kàwé òfin.. | wikipedia | yo |
Ailrinrin ko pari ile-ẹkọ giga rẹ nitorinaa o ṣe idiwọ fun un lati gba oye Ile-ẹkọ giga na.Iṣẹ ninu ifọrọwanilẹnuwo kan, Oattarinrin ṣapejuwe ìfẹkùfẹ rẹ fun ṣiṣe ṣaaju iṣafihan ni ifowosi ni ile-iṣẹ fiimu Yoruba ti Naijiria; awakọ akọkọ eyiti o mu ki o wa sinu ile-iṣẹ yẹno ni iberu fun osi.. | wikipedia | yo |
Ailrinrin jẹ olupilẹṣẹ fiimu ti o se ọpọlọpọ awọn fiimu; fiimu naa ni akọle rẹ rẹ jẹ "owo naira bet ti o mu ki ailagbokan rẹ lagbara bi olupilẹṣẹ fiimu bi fiimu ṣe gba awọn atunyẹwo rere ti ọpọlọpọ.. | wikipedia | yo |
Ailrinrin se awon fiimu miiran bii Ọláníd Chets, Gold, Iyawo abuké, Tinubu, ọlẹ̀, De First Lady ati owo naira BET.Orogún ni osu Kesan ojo 21, 2019, Punch Print Media publication described the Feud Between Ailrinrin and Toyin Abraham as "The Biggest Feud in the Nigerian Yoruba Movie Industry" in 2019.. | wikipedia | yo |
The misunchartsding between ihòrin & Tóyìn Abraham required the intervention of accomplished Actors and the Yoruba movie industry Veterans such as tòótọ́ làníyàn, and ìyá Rainbow to mediate in their dispute.Àwọn èbùsi ayé ara ẹni Adévrinrín jẹ́ òbí anìkàntọ́mọ.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013 o yipada lati Kristiẹniti si Musulumi o gba orukọ AISHH eyiti o se apejuwe si The Punch awon oniroyin iroyin ti Naijiria bi "orukọ Musulumi".ti yan fiimuiwoye The Dance Movie Project (2016) as Mrs.Balogunbuwn (2010)Tolani Kolòjòdi abuké Tinubu: De first ladmo naira betarewa ejo (2009)Iṣẹ onise (2009)Awon itọkasi awon eniyan Alààyè Omo abẹ́ Unàwọn ará Naijiri osere ara Naijiri ona asopọ ita.. | wikipedia | yo |
UzoAmaka Doris Aniunoh jẹ onkọwe ati oṣere ara ilu Naijiria.. | wikipedia | yo |
O ti di Odu ti kin ṣe àìmọ̀ folóko ninu ere MTV Shuga leyin ti o ti han ni ọpọlọpọ awọn ẹya ere Telifisonu naa to fi mọ akọkọ ati Eyipada.Igbe Aye rẹ Aniunoh ni a bi ni Onitsha.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2015, o lọ si UK nibiti o ti keeko iwe kiko ni Yunifasiti Birmingham ti o si gba oye giga.ere sise re o pada si orile-ede Naijiria ni odun 2017, o si lọ si awon ayewo ti o si sile fun ti ere alatigba-dègbà tuntun ti a pe ni MTV Shuga.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe kòkòńgẹ́ láti wà lára àwọn tí wọ́n yàn, ó sì kópa Cynthia.. | wikipedia | yo |
O ti gba ìmọ̀ràn tẹ́lẹ̀ rí láti ẹnu nìyí Akínmọkan ní ìmúrasílẹ̀ fún àyẹ̀wò náà.. | wikipedia | yo |