cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní oṣù kejì ọdún 2015, ó ṣe orin kíkọ ti orí ìtàgé gẹ́gẹ́bí olórin agbeya fún ìgbà àkọ́kọ́ ní Mali, ní Festival Sur lé Nigerni Segọ́ú, níbi tí oti kọrin pẹ̀lú ọ̀rẹ́ ẹ̀ ti ọjọ́ Tope àti àní tí on wo àwọ kọ́ṣe e, Oumou tìntìn, Baskou Kouyate àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórin tí ó wá láti ìlú Málì.Nínú àwọn orí ẹ̀, Diawara man soro nípa wàhálà tó wà nínú lólò, Inilo fun owó fún arawa, wahala tí àwọn obìnrin ilẹ̀ Africa man se; ìgbé ayé lábẹ́ òfin ẹ̀sìn àti ìwà dídábẹ́ fún ọmọ obìnrin..
wikipedia
yo
Ninu orin e kan "Mali-ko (Peace/La Paix)" orin yi gun fun iṣẹju meje, ere orin e na soro nipa iṣẹgun ariwa Mali, o so pe ki a pa ina ikorira ti a ni si awon ara Tuareg, ti o so pe awon lo fa ilolu won..
wikipedia
yo
"Fatoumata Diawara Reinvented", FIFI Sque, April 8, 2009, accessed June 8, 2011.
wikipedia
yo
"Oumou tìnmélékì, Barbican Hall, London", The Independent, April 28, 2009, accessed June 8, 2011.
wikipedia
yo
"Afrocubism", Worldmusic.co.uk, accessed June 8, 2011.Àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1982Pages with unreviewed translations..
wikipedia
yo
Fred àìsàn jẹ́ òṣèré, olùgbéré-jáde àti adarí eré ọmọ.Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ nínú ìmọ̀ eré oníṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Jóṣ, ó di ìlú-mọ̀ọ́ká ní ọdún 1986 nínú eré legacy..
wikipedia
yo
Bovi je alawada, osere, ati onkowe omo orile-ede Naijiria, o ti gbe eto man on fire kan to gbajumo jake-jado agbaye.ibẹrẹ aye ati Eko Revi Ugbóná ni won bi nu ilu bini ti o je olu ilu fun Ipinle Edo, o lo si ile-eko alakoobere ti Uniben ni odun 1991, o tun wole sile-eko ti ijoba apapo ilu Uugh ni Ipinle Delta, awon obi re mu kuro ni ile-eko yi lo si ile-eko girama ti Edokpọlọr ni ilu bini ti won n gbe, ki won le baa moju to..
wikipedia
yo
Àmọ́ ẹ̀kọ́ kò ṣojú mímú fún ni wọ́n bá tún mu sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti onícha-ọlọ́nà
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó parí ilé-ẹ̀kọ́ náà, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ní ọdún 1998 ní ìpínlẹ̀ Delta níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣẹ́.Iṣẹ́rẹ́rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aláwàdà ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àwàdà ṣiṣẹ́ ní inú oṣù kẹrin ọdún 2007, níbi tí ó ti kọ́kọ́ fara hàn nínú eré extended Family, tí ó jẹ́ wípé òun náà ni ó kọọ́ tí ó darí rẹ̀ tí ó sì gbé jáde.
wikipedia
yo
Eré náà gbajúmọ̀ gidi, nígbà tí yóó fi di ọdún 2008, Bovi tí n kópa nínu àwọn ètò ìru-ó-kàn káàkiri ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó di gbajú-gbajà látàrí ipa rẹ̀.nínu ètò Nite of 1000 Laughs tí ọ̀gbẹ́ni Ọ̀pá Williams gbé kalẹ̀ ní ọdún 2013..
wikipedia
yo
Nínú ètò kan tí òun náà gbé kalẹ̀ tí ó pè ní Bovi- Man on Fire ní ọdún 2014, ni ó ti ṣe àfihàn àwọn òsèré olórin Nàìjíríà-Nàìjíríà bí jáRu àti Askáríayé hàn..
wikipedia
yo
Eto yi ti fun BOvi ni anfani lati ṣe irin-ajo lọ si awọn orilẹ-ede bii Amẹrika, London, MelBourn ati Toronto ni ọdun 2017..
wikipedia
yo
Wọ́n tún yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ yí fún ìgbà kẹta fún iṣẹ́ tí ó yàn láàyò.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ìtàkùn ìjásóde Twitter Pageàwọn Ọjọ́ìbí ní 197921st-Century Nigerian Malé Actorṣàwọn Ènìyàn Aòkèèrèmale From Delta Stata Stagg Actors CocethiNigerian Directors, Tímber Writers..
wikipedia
yo
rẹmi Abiola (Oṣù Kẹẹ̀jọ Ọdún 1953 – Oṣù Keèje Ọdún 2009) jẹ́ òṣèré fíìmù ti ìlú Nàìjíríà àti ìyàwó olóògbé Moshood Abiola, ẹni tí ó ṣe pàtàkì nínú olùṣòwò àti olóṣèlú ìlú Nàìjíríà..
wikipedia
yo
rẹmi? kù sí ìlú New York ní ọjọ́ mọ́kàndínlọ́gbọ̀n, Oṣù Keèje, Ọdún 2009 lẹ́hìn tí ó pàdánù Ogún pẹ̀lú Àìsàn Cancer..
wikipedia
yo
Ó fi àwọn ọmọ méjì sáyé lọ tí orúkọ wọn sì ń jẹ́ Abimbola Umardeen àti Olajumoke Adetoun.Iṣẹ́ ìṣe rẹmi kọ́ṣẹ́ òṣèré ní ilé-ìwé tó ń bẹ fún eré orí-ìtàgé ní ìlú England ní àwọn ọdún 70 lẹ́hìn tí ó kúrò ní ìdí iṣẹ́ Nigerian Airways gẹ́gẹ́ bí olùtọ́jú ẹ̀rọ Baata..
wikipedia
yo
Nígbàtí ó padà wá sí Nàìjíríà, ó ṣe afẹ́rí àwọn ipa ó sì tún kópa nínú eré tẹlifíṣọ̀nù tí Báyọ̀ Awalà àti olóyè Tunde Olódé olóyè, èyítí wọ́n gbé jáde lóri NTA Channel 10.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1953àwọn Ọjọ́ko ní 2009Nigerian Film Nmber Filmmakers Actres In Yoruba Yoruba Cinlle-Century Nigerian Actresses-Century Nigerian Actresses From Cancer Inl New York (State) ↑ Un unre; ní translations..
wikipedia
yo
Nneka Julie Adams (tí a bí ní 8 Oṣù Kẹẹ̀jọ) tí a mọ̀ ní Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ gẹ́gẹ́ bi Nneka Adams tàbí Nneka J..
wikipedia
yo
Adams je osere omo Naijiria ti o wa ni ilu Kánádà, onkowe fiimu, o si n se fiimu..
wikipedia
yo
Oruko re tan daada julo fun awon ipa re to ko ninu awon fiimu bi Black Men Rock, Flight Last to Abuja ati Nation Under Siege.ibẹrẹ Aye rẹ Adams dagba ni Ipinle Eko, awon obi re ṣii wa lati Ipinle Delta, Naijiria..
wikipedia
yo
Adams lọ si ile-eko giga MaryMount, o si lo si Yunifasiti ti ilu Eko nibi ti o ti gba oye-ẹkọ ninu ìmòye..
wikipedia
yo
Ní àkókò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò fún àwọn ipò iṣẹ́ ní Nollywood, èyí tó ṣokùn fa ipa àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ìgbà WAwá lọ́mọdún mẹ́tàdínlógún (17).Iṣẹ́ iṣẹ́ ó dá ilé-iṣẹ́ Adams Film Production sílẹ̀, ilé-iṣẹ́ kan tó n rí sí fíìmù, tẹlifíṣọ̀nù àti ìpolówó..
wikipedia
yo
Lori ile-iṣẹ naa ni o ti ṣe fiimu, "Black Men Rock" ní ọdún 2017 tó ṣe ìfihàn John Dumel, Ruth Kadiri, Boláńlé Nọbalọ́wọ́ àti Beverley Oṣù..
wikipedia
yo
O tun ṣe fiimu "The Devil in Between" ni èyí tí òun funralararẹ, DeYemi kèfèrí àti ik Ogbonna dìjọ kópa nínu rẹ̀..
wikipedia
yo
Lára wọn ni Chronicles of Vendata, Ruth, If You were Mine, Perfect Combo, a Nation Under Siege ati Last Flight to Abuja.Àkójọ eré àwọn àṣàyàn eré rẹ̀The Gentlemanhis Queenthe ListBlack Men Rockthe Devil in BetweenRuth Flight to Abujaif You Were MineChronicles of Vendatáa Nation Under Sid’’àwọn Ìtọ́kasí Nigerian Television Actresses of Birth Missing (Living People)Àwọn Ènìyàn Alààyèd Fromtime From Loneppa of Lagos Alu-Century Nigerian Actresses..
wikipedia
yo
chet Aroko jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a tọ́ dàgbà ní ìlú New York ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
AdeJùmọ̀kẹ́ Adeunun jẹ́ òṣèré ọmọ Nàìjíríà kan, tí a bí ní Abeokuta, Ìpínlẹ̀ Ògùn Nàìjíríà, níbití ó ti ní ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé gíga..
wikipedia
yo
Oruko re tan daada julo fun ibeji ipa gege bi Esther ati kedechi ninu awon gbajumo ere telifisonu Nollywood ti n se Jenifa's Diary ati InduStreet..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó kópa gẹ́gẹ́ bi Jumymy Adams ninu eré Nollywood aláṣeyọrí kan tí ń ṣe Alákadá 2 Ìlànàlo pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé, Tóyìn Abraham, Odunlade Adekola, Linda Yẹsty, Falz, Juliana Oyọ, Ọmọ́túndé Ama David (lòlò) àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.Ó kọ́kọ́ rí ìdánimọ̀ gẹ́gẹ́ bí "Jíjídé" nínú fiimu Tunde Tunde, Dazzling Mirage ti ọdún 2014 pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Kúnlé Afọláyan, Kemi Lala Akindoju, Taiwo Aja-Ice O-Tgbin, Seun àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. Àyè àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bi AdeJùmọ̀kẹ́ sínú ìdílé Olùṣọ́ Olùṣọ́ ni Oṣù kèéta, Ọjọ́ kẹrin, ní àwọn ọdún 80 ní ilé-ìwòsàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Sacred-W6] ní ìlú Abeokuta, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà.adé ló sì àwọn ilé-ìwé Aladáni Alaf Banamtes ní Ìlú Ìbarà, Abeokuta; Abeokuta Girls *'Grammar School, Onidélé, Abeokuta; Ṣáájú kí ó tó lọ láti gba oyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ International Relations láti Yunifásítì Ọbáfẹ́mi, Ilé-Ifẹ̀, Ilé Ọ̀ṣun Osun..
wikipedia
yo
O tun gba ifọwọsi ninu ṣiṣe fiimu lati la CineFabrique Multimedia Cine ni Ilu Lyon, Orilẹ-ede Faranse ni ọdun 2017 lẹhin ti o gba ẹbun Sidersepu ti Ford Foundation ni bi ayẹyẹ Africa International Film Festival ni ipari Ikeẹkọ rẹ fun fíú ṣiṣẹ́, eyi ti DSl ṣe fun awọn ọdọ oni fiimu ti Naijiria ni ọdun 2016..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ere sise gege bi akosemose lehin ayewo Tunde Kelani fun fiimu Arugba ni odun 2008 nibi ti o ti ko ipa Ọmọọba MoBándélé pelu ajọṣepọ Bukky Wright, Bukola AwoYemi, Segun Adéfilá ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.iṣẹ-iṣẹ AdeJùmọ̀kẹ́ ri idanimọ ni ọdun 2016 fun Asiwaju ipa rẹ gege bi Esther ninu ere telifisonu alawada kan ti akole rẹ n je Jenifa's Diary..
wikipedia
yo
AdeJùmọ̀kẹ́ Adeunun ti kópa nínu fíìmù tó lé ní mẹ́wá (lédè Gẹ̀ẹ́sì àti lédè Yorùbá) gẹ́gẹ́bí òṣèré..
wikipedia
yo
O sise igbohun safefe ni ile-iṣẹ Idanilaraya "My presenter" fun ere telifisonu kan kan labẹ isakoso Daniel ni odunmin ni odun/2011..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó ṣiṣẹ́ ní Radio Concert (ile-iṣẹ redio ori ayelujara kan ni Naijiria ) lati ọdun 2012 titi di 2015..
wikipedia
yo
Lẹhin naa, o tẹsiwaju lati ṣe apa kini ere rẹ ti akole rẹ jẹ The Doke with Jùmọ̀kẹ́, ere idaraya kan ti o ni awon ifọrọwanilẹnuwo ati awọn imọran ìtúnraṣe, ni ọdun 2012.Awon aṣayan ere rẹ InduIndust (2017)The Ex (2015)Jenifa's Diary (2016)Oluka 2 (2013)W of My Dreams (2013)Dazzling Mirage (2014)The Unwritten 1&2 (2009) ots= series series (2008)gba (2008)Awon ẹbun ati awon yiyan a yan fun osere ti o dara julọ ni bi bi ayeye fiimu ti Afirika ni Dallas, Ilu Texas (2016) a yan fun Ifihan Odunde, níbi ọdún àwọn ẹbun Bori, Nàìjíríà (2015) Olùborí ti ẹbun Mayàá Mayàá 4.0 Oju Tuntun ti Nollywood (2016) Olubori ti ẹbun Maat Ojú Tuntun ti Nollywood (2017)ìgbésí Ayeìgbésí ara ẹni Adeun-Muko kọ́ ko si tii ni àfẹ́sọ́nà tabi Ko L. ↑ Ìtọ́kasí àwọn oṣere ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹ̀sán-an, Ọdún 1959) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sì lọ́lá ìdíje jẹ́ òṣèré onítíátà Nàìjíríà lobinrin àti àǹtí fún òṣèré onítíátà Nàìjíríà lọ́kùnrin Kúnlé Afọláyan..
wikipedia
yo
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn tí ó kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bi Madam Adisa nínú fíìmù 1995 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Deadly Affair.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Yvonne Jẹ́gẹ́dẹ́ jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, Model àti adarí ètò lórí ẹ̀rọ amóhùmáwòrán-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jẹ́gẹ́dẹ́ di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ère kan tí ó gbé jáde tí ó pè ní 3 Is Company..
wikipedia
yo
O di eni aye n fe leyin ti o kopa ninu fọ̀ràn awo orin African Queen ti gbaju-gbaja Olotin 2face Idibia ati Annie Macaulay gbe jade.ibẹrẹ aye ati ẹkọ rẹ won bi Yvonne Jẹ́gẹ́dẹ́ ni ojo kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n Oṣu Kẹjọ ọdun 1983 ni agbegbe Agenebodè ni Ipinle Edo, ni orile-edeNaijiria ..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìpínlẹ̀.Èkó, tí ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè níṣe ẹ̀kọ́ Yunifásítì Yunifásítì Cyprus, nínú ìmọ̀ “International Relations rẹ̀ Jẹ́gẹ́dẹ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ní ọdún 2014 níbi tí ó ti kópa nínu eré Missing Angels..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó tún fara han nínú fọ́nrán àwo orin African Queen ti gbajúmọ̀ olórin 2face Idibia tí wọ́n tún mọ̀ sí 2Bàbá gbé jáde ní ọdún 2005..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó gbé eré tirẹ̀ jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní 3 is company tí ó sì kópa nínú eré náà gẹ́gẹ́ bí olú-ẹ̀dá ìtàn Where She Starred as the Lead Character.Ní ìparí ọdún 2016, Ìwé ìròyìn ìgbafẹ́ ti Genevieve Nnajiyàtọ̀ sí eré ṣíṣe, Yvonne Jẹ́gẹ́dẹ́ ò ti fara han nínú fọ́nrán àwo orin "gọ̀ẹ́ tí olórin ilẹ̀ Nàìjíríà djìnjin àti fọ́nrán àwo orin kokosẹ̀ tí Sound Sultan gbé jáde.Àwọn eré tí ó ti kópa Missing Angels–s of Lagos3 is comse Com's Law of life Staeẹ̀sìde Chic Squsingle and Married10 Days in sun city the fight for the Family Soon s-the Sassy One-ìdárayá to America Ex-Kó-Kóka-Kóka MeTrue Vess of Sweet Love Shtwo that Binds togetherst Ṣìgust Kábtes àwọn Ọjọ́ìbí ní 1983 ní 1983 alààyè of film Act, film Tígi O personali of Cyprus Shu..
wikipedia
yo
Paul Igwe won bi Paul Igwe ni ojo ketadinlogbon osu Kọkànlá odun 1977..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùgbéré-jáde, ònkọ̀wé, àti ẹni tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún dídarí ètò orí èrò amóhùmáwòrán-máwòrán, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni o ni ere olosoose ti akole re n jẹ clinic matters, the Bewbrays, Ọjays àti asunder" tí ó sì darí àwọn eré náà.
wikipedia
yo
Iṣe rẹ ni ọdun 2000, o bẹrẹ Ile-iṣẹ igbẹrẹ-jade rẹ ti o pe ni Whitestone Cinema ti o ti dari ati gbe ere ti o to ogun jade pẹlu awọn ere olosoose ti o to mẹjọ jade..
wikipedia
yo
Igwe di gbaju-gbaja ni odun 2000 leyin ti o kopa ninu ere kan ti akole re n je "Outrageous", ati ipa laami-laaka ti o ko ninu ere olosoose ti akole re n je "extended Family" ti o je ere onípele mọkandilogoji ni odun 2007..
wikipedia
yo
ó dá ilé-iṣẹ́ sinimá tirẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 2009, ó sì kọ́ èrè ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tirẹ̀ Clinic Matters tí ó ń gbé jáde láti ilé-iṣẹ́ rẹ ní ọdún 2009..
wikipedia
yo
Eré yí tí gba àmì-ẹ̀yẹ oríṣiríṣi labele àti loke okun tí ó fi mọ́ àmì-ẹ̀yẹ '''World Ququality commitment Award ní orílẹ̀-èdè Paris ní ọdún 2018.Ní inú oṣù kejì ọdún 2012, ó gbé eré olosoose rẹ̀ keji tí ó pè ní The Benjamins, eré tí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards fún eré onípele tí ó dára jùlọ.Ó bẹ̀rẹ̀ eré onípele míràn tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Ọjàys ní ọdún 2015 tí wọ́n yàn yàn eré náà fún àmì-ẹ̀yẹ NAFDA Awards fún eré onípele apani-lẹ́rìn jùlọ..
wikipedia
yo
Paul tún gbọ̀nà ara yó pẹ̀lú bí ó ṣe gbé àkànṣe ètò kan kalẹ̀ tí ó pè ní "Usekwu igbo", tí ó túmọ̀ sí iyàrá ìdáná igbó..
wikipedia
yo
Eto yi naa ti ami-eye ti 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards fún eto ori ero amóhù-máwòrán ti peregedé jùlọ ní ọdún 2016, èyí tó wáyé ní gbọngan Eko Hotel ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Paul tún gbé eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ onípele mìíràn jáde ní ọdún 2016 tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní House 6..
wikipedia
yo
O tun gbe ere olosoose miran ti o pe ni asunder ti o n ṣafihan ẹbi ati igbeyawo ẹbi kọkàn jade ni ipari ọdun 2019 yi kan naa..
wikipedia
yo
O gbe ere onípele miiran jade ni ede Igbo ti o pe akole ere naa ni "Nkẹwa" ni ọdun 2017, ti wọn fi han ni ori Africa Magic Igbo..
wikipedia
yo
Oun naa lo dari ere ti akole re n je"Dance To My Beat", Ere ti Joseph Benjamin, Kehinde Bankole, Tóyìn Abraham, àti Mary Remmy Njoku ti kopa.Awon aṣayan ere rèé tun le wo list of Nigerian Film producersáwọn itọkasiàwọn Ìtàkùn ìjásóde awon Ọjọ́ìbí ni 1977àwọn Eniyan Alààyè, Film Directors, Film producersbusinesspeople from Lalesígbó BusinessPeople-Century Nigerian Businesspeople-21st Nigerian AcguopSouth Television company Widers..
wikipedia
yo
Bisi Kuri, tí a bí ní inú ọdún 1986 jẹ́ òsèré orí-ìtàgé, olùdarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bisi di ìlú-mọ̀ọ́ká lẹ́yìn tí ó kópa nínu eré ìgbko ti dàrú àti Aramotu igboro ti dàrú and Aramotuìbẹ̀rẹ̀. Ayé ReBisi ni ó jẹ́ àbílé kejì áwọ̀ obì rẹ̀ nínu àwọn ọmọ márun ùn tí àwọn òbí rẹ̀ bí ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìlú Ìbàdàn kan náà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-èkó Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó (LASU) níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú Business Administration.Iṣẹ́ ReBisi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ tí ó sì di ìlú-mọ̀ọ́ká nínú eré oníṣe nígbà tí ó kópa nínú eré ìgboro ti dàrú, àti ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olú ẹ̀dá ìtàn nínú eré BỌlọ́dẹ ó kú, àṣírí owó, Èbúté, Ẹja Tútù atu ọká..
wikipedia
yo
Bisi's Acting Career shot into limẹ́lì after she starred in the movie igboro ti dàrú..
wikipedia
yo
She went on to play leading Roles in films including bỌlọ́dẹ o'ku, àṣírí owó and ebute..
wikipedia
yo
She was Nominated in the "Revelation of the year" Category at the 2009 Best of Nollywood Awards and in the "Best Lead Actress in a Yoruba film" Category at the 2012 edition.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti Ìfisọrí Reiku Rebísí Kọ́mọláfẹ́ Morọ kan ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2012..
wikipedia
yo
Ó papọ̀ da látàrí ipò ìlóyún tí ó wà, gẹ́gẹ́ bí gbogbo àwọn ìwé-ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀..
wikipedia
yo
ó papò dà ní ilé ìwòsàn ìkọ́ni ti ìlúIbadan tí wọ́n sì sin-ín ní ọjọ́ kẹrin osù kíní ọdún 2013..
wikipedia
yo
in Ìbàdàn.Àwọn Aṣayan eré rẹ̀ ìgboro ti dàrú ayé ọ̀rẹ́ méjì àpèrè orí ọmọ ọlọ́mọ lãrín èrò jọ kín jọ ake bỌlọ́dẹ o'ku aramotu àṣírí owó ọgbẹ́ inú aiyédì látọ́nwá alákadá Mofẹ́ jayò Èbúté Ìbẹ̀rù Bód Ayé rẹ̀K ṣe Ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Tunde Odun tí ó fi orílẹ̀-èdè Canada ṣe ibùgbé, àmọ́ tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.Ẹ tún le wo List of Nigerian Film producer itọka Moseeré filmmakers Actόsa In Yorùbá Nígb-21st Nigerian Act (ARorali from Ìbàdànàwọn Ọjọ́ìbí ní 1986àwọn Ọjọ́lẹ Aláìsí ni 2012 State Aludára in Child Burubù in Oyo
wikipedia
yo
tomi Araga ti won bi ni ojo kẹrinlelogun osu karun-un odun 1987 je osere ori-itage, olorin, òǹkọrin ti gbogbo eniyan mo si salewa ninu ere onípele olosoose ti Tinsel.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọ́n bi tomi ni ojo kẹrinlelogun osu karun-un odun 1987 ni ipinle ogun..
wikipedia
yo
Ó lọ sílé ẹ̀kọ́ Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè (lingistics) àti èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀, tí ó sì mú èdè Yorùbá ní ìṣe Àsàyàn..
wikipedia
yo
TerraKulture BIP Agboro ere rẹ tinsense ohun miiran ti tomi tun n se ni o je oludasile CGT Media Ltd, African Entertainment and media company.Awon itọkasiawon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1987Nigerian Film ActressesYorùbá Actresses-Century Nigerian Act ofversity of Lagos alumni..
wikipedia
yo
Afro Candy (tí a tún kọ́ ní AfroCandy), jẹ́ òṣèré fíìmù ti ìlú Nàìjíríà, olùdarí eré, akọrin, afẹwàṣiṣẹ́ àti òṣèré oníhòhò..
wikipedia
yo
O jẹ oludasile ati alakoso ti awọn Invisible Twins Productions LL.ibẹrẹ Aye ati Eko re Afro Candy ni a bi ni Umudúrúebo Ugírì-Ike, Ijọba Agbegbe IkeDuru ti Ipinle Imo..
wikipedia
yo
Nígbà tó wà lọ́mọdé ní ilé-ìwé òko wáwá, ó ní ẹ̀mí iṣẹ́ fún eré ìtàgé ṣíṣe ṣùgbọ́n ó pàdánù rẹ̀ lẹ́hìn títẹ̀ ilé-ìwé gíga..
wikipedia
yo
ó gba oyè-ẹ̀kọ́ ní ìṣàkóso ọ́fíìsì àti òye-ẹ̀kọ́ ti ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ ní ìṣàkóso ọwọ́..
wikipedia
yo
Ní àfikún, ó kọ́ ẹ̀kọ́ bi òṣìṣẹ́ ààbò.Iṣẹ́-iṣẹ́ nígbà tí AfroCandy Dwári nípasẹ̀ ilé-iṣẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ King George Models, wọ́n gbà níyànjú láti lépa iṣẹ́ òṣèré..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́, ó sì kún ní àwọn ìkéde fún àwọn ilé-iṣẹ́ bíi Coca-cola, Tolọ́kùnrinl àti Liberia Gsm..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀ sí tẹlifíṣọ̀nù, níbití ó ti kó àwọn ipa kékeré..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2004, ó kó àkọ́kọ́ ipa pàtàkì nínu fíìmù gẹ́gẹ́ bi Susan nínu fíìmù Dangerous Sisters tí Obi obìnali ṣe ìtọ́sọ́nà rẹ̀..
wikipedia
yo
Awon ipa re miiran tun ni nneoma, ọmọbirin Abule kan ninu fiimu End of the Game ati Jezẹbẹl ninu fiimu dwelling in darkness and Sorrow ni odun 2005, o darapọ mọ ọkọ rẹ ni Amẹrika, eni ti o ni ọmọ meji pẹlu..
wikipedia
yo
Lẹhin àwọn ọdún meji ti o fi gbé nibẹ papọ̀, oun ati ọkọ pinya..
wikipedia
yo
Mazmúra tun ti han ni awọn fiimu bii deìríra Instinct, how did I get here, ordeal in Paradise, the Goose that lays the golden eggs ati pe o ti ṣe àwọn ipa kekere ní oríṣiríṣi sinimá Hollywood..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi akọrin, akoko orin àdákọ rẹ̀ "Somebody help Me" jẹ gbigbe jade ni ọdun 2009 ti atẹle rẹ jẹ akoko akojọpọ orin rẹ, eyiti o ṣe agbejade gbajugbaja orin alaṣeyọri rẹ kan "IkeBe na moni"
wikipedia
yo
Pàápàá ní ọdún 2011, ó ṣe àgbéjáde orin àdàkọ “voodoo-Jùjú Woman". sí eré ṣíṣe àti orin, Mazmúra ń ṣiṣẹ́ bí alamọja kóòdù.Àkójọ eré dwelling in darkness and Sorrowdangerous Sisters (2004)The Real Pvrend of the Game (2004)Between Loveted must shakemy experience CrimeBeyond Green Pastudekìíkìí InstinctQueen of Zamúnding Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
O jẹ anfani yiyan fun oṣere lobinrin ti o dara julọ ni ipa atilẹyin ni bi 12th Africa Movie Academy Awards..
wikipedia
yo
O tun gba ẹbun Oṣere ti o ni ileri julọ ni bi 2014 Best of Nollywood Awards..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, ó ṣe ìfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lójú amóhù-máwòrán nínu eré tẹlifíṣọ̀nù elDorado..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọkan lara awọn ẹgbẹ aṣa ni ti 2012 London Olympic Games.Igbesi aye rẹ Agu ni akọkọ ninu awọn ọmọ marun-un ti obi rẹ..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi ijabọ ti Pulse Nigeria, Agu dagba ni Ilu Benin ati Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Ó ní oyè-ẹ̀kọ́ nínú Biochemistry láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Nnamdi Azikiwe ní ọdún 2007..
wikipedia
yo
Ó tọ́kasí bàbá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹni tó fún ní ìgboyà láti ṣe iṣẹ́ eré ìtàgé..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Agu ṣe sọ, iṣẹ oṣere rẹ bẹrẹ ni ori ipele ni Benin ni ọmọ ọdun 14..
wikipedia
yo
Nigbati o n sọrọ si The Nation (Nigeria) Lori ibalopọ ẹlẹ́yà kan naa ni Nollywood, Agu ṣapejuwe iṣẹ́ naa bi ẹṣẹ lori awọn ipilẹ ẹ̀sìn ati pe ko ro pe ofin rẹ jẹ Ìrúfin Awọn ẹ̀tọ́ eniyan..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀, ó sọ àsọyé pé kò yẹ kí wọ́n rí bí ìwà ọ̀daràn bí ó ti ń ṣe ṣẹlẹ̀ ni Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Pombajira, Pombogjira, Pambujira, Pombujira, Pombojira, Bombogira, Pombagira tabi Inzila (em), ninu itan aye atijọ ti Bantu.ijosin rẹ yatọ, pẹlu diẹ ninu awọn ile ti o ṣe akiyesi rẹ bi Ọlọrun ati awọn ọmọ rẹ ti ipilẹṣẹ nipasẹ rẹ, ati ni awọn miiran bi nkan, eyiti o wọ inu iranran ti ohun-ini ni awọn eniyan ti a ko ya si mimọ fun u nipasẹ awọn ọna ibẹrẹ..
wikipedia
yo
Pombajiras ati Exus ni apapọ tọka si ni Umbanda bi awon eniyan ita...
wikipedia
yo
WMAST Montsho (Bii ni ojo kokandinlogun osu kewaa odun 1983) je Akowe, osere ati adari ere fiimu) ni orile ede South Afrika.won bii si ilu Sòwẹ́tò..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Greenside High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of South Africa níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Audio-Visual Multimedia..
wikipedia
yo
O gba ami eye Best Achievement in Script in a TV Drama láti ọ̀dọ Golden Horn Award..
wikipedia
yo
Ztsan Mcfenroro (Bii ni ojo Kọkànlá osu Kẹwàá odun 1985) je osere ati modeli ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa NoLunda Memela tí ó kó nínu eré Generations.Wọn bíi Mfenna sí ìlú Johannesburg..
wikipedia
yo