cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Yvonne Okoro wa lati AmanKalu Alayi ní Ìpínlẹ̀ Ábíá, Ilu Nàìjíríà.Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré tí ó dára jù lọ ní ọdún 2010 ní Ghana Movies Award.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì yàn fún òṣèré ti odara julo fun Africa Movie Academy Awards lẹsẹsẹ ní ọdún 2011 àti 2012 fun awon fiimu Pool Party àti Single Six O ti gba ami ẹ̀yẹ mẹ́rin lati ọ̀dọ̀ Africa Magic Viewers' Choice Award ni odun 2012 won fun ni ami ẹ̀yẹ fún ipa ti oyàtọ̀ ni Nigeria Excellence Awardsiìgbésí aye Ìbẹ̀rẹ̀ nitori iya e je omo Ghana ti baba e sin je omo Naijiria, oje omo iran àwẹpo, nitori idi eyi ni ófi man pe ara e ni omo Africa Owa lati ebi ti o tobi, ohun ni akobi iya e, osi je elekarun fun baba e.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà tí ọtí wà ní ọmọdé ní ọtí fẹ́ràn kí Oguọ ṣe eré.. | wikipedia | yo |
Olosi Achimota Preparatory School, lehin nah o lo si Lincoln Community School lehin na olosi Faith Montessori School.. | wikipedia | yo |
O losi Mfantsiman Girls Secondary School lehin LÓRÍ na ni owa lo si University of Ghana, Legon ni ibi ti oti gba oye Awonran, pelu ede ati imo-ede.. | wikipedia | yo |
Ótún lọ sí Universite de Nantes ní Fránsì láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ní pa ìròyìn, eré àti títà ọjà.Iṣẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré ní ọdún 2002, eré tí ó kó kópa nínu ẹ̀ ní Sticking to the Promise, eleyi ti Theo Akatungba darí tún kó ipa kékeré nínu jara Tentacles, tí Theo Akatungba darí, Point Blank Media Concepts ni ó gbé jáde.Ó n ṣe agbàlejò eto ṣíṣe oúnjẹ kan, ròkun and Braggarts | wikipedia | yo |
Eto yi je eto ti awon gbajumo man wa lati se orisiri ounje, won osi ma soro nipa nkan orisirisi ton sele ni awujo.Awon owo imi o so fun ile ise redio, Peace FM ti o wa ni Accra pe ohun ni ile ise ti ti ohun Deusaur company Limited.. | wikipedia | yo |
2012) With HLolo Dandala.I broke my Heartàdáms APtẹ́nì Film series (2011-2012)Crime must go (2016)Rebecca (2016)àwọn ìtọ́kasí àwọn ẹ̀nìyàn alààyẹ̀.. | wikipedia | yo |
Comrie. Àwọn Èdè àkọ́kọ́ ti South Asia, àárín ila-oorun àti Áfíríkà .. | wikipedia | yo |
Sydy Emade (tí a bí gẹ̀gẹ̀ bi Elone Synthia Emade ní Ojo kankanlelogun Oṣù kankanla Ọdún 1993) jẹ́ òsèré, àwòṣe àti agbe eré jáde ọmọ ìlú Cameroon.. | wikipedia | yo |
Àwọn eré tí oti gbé jáde jẹ́ A Man For The Weekend and Rose on the Grave.. | wikipedia | yo |
O jade ninu ere Nigeria Nollywood ni ọdun 2016 ninu ere "Why I Hate Sunshine" Ni odun 2017, won ko oruko e kale gegebi osere keji ti o sise ju ni ilu Cameroon, awon agbere jade ori ero ayelujara Njoka tv fun ile Afrika won fun ni ami eye osere obirin ti o dara julo ni ile Cameroon, ni ami eye Scoos Academy ni odun 2017.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye yeye ini ti Cameroon ni odun 2014.Iṣẹ Ere ti Emade ko se ni ere "Obsession" ti o jade ni odun 2010 ohun ni Alaga ati oludasile Blue Rain Entertainment.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017 ó gbé eré A Man For The Weekend jade eleyi ti oni osere Nollywood Alexx Ekubo ninu e.Àṣàyàn eréọdún 2017 a man for the dọ́wẹ̀ẹ́kẹ̀ńdọdún 2016 Bad Angel (jara) Soldier wife House mate Smokesscreen before you say Yes Chaising tail 2015 die Another day a Kiss From Rose Chaising tail 2014 Why I Hate sunshine Rose on the Grave different kind of men (2013) Pink Poison with épúle Jeffrey (2012) Enrokod Obsession (2010)awards àti ti idanimoàwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1993.. | wikipedia | yo |
Lucie Memba Bos je osere ati Afarajade omo ilu Cameroon ti won bi ni odun 1987, oti kopa ninu awon ere ede Faranse ati ede geesi won ye si pelu ami eye osere iwaju ti o dara ju ni Cinema titi Cameroon fun awon ẹ̀ṣẹ̀rẹ̀ ele Faranse ni Cameroon Movies Merit Award (CMMA) titi odun 2013.. | wikipedia | yo |
O ko ipa ninu ere Nollywood ti akori re pink Poison pelu Jim Iyke ati Far pelu Dakore Akandeni odun 2014 o se ifi lole L.M.B production, eleyi ti o so ni oruko e.. | wikipedia | yo |
O se agbejade ere Cameroon ti akori e je Paradise, ni odun yi na ose agbejade ere LA Patrie D'Abord, ere ogun ti won fi ranti awon ajagun Cameroon ni odun 2017, won yan fun osere birin ile Cameroon ti o dara julo fun ami eye Trophphees Francop’ko du Cinema, fun ipa re ninu ere La Patrie d'Aboìgbésí Aye ibẹrẹ won bi Lucie ni DSgg West Region titi Cameroon osi dagba si Bafoussam ibi ti oti bere ise modeli lehin na ni obere ise osere.. | wikipedia | yo |
O ga oye-oye ni Baccalaureat Philosophique owa ko lo si ilu Douala fun awon ise imi.. | wikipedia | yo |
Ko si alaye llori ojo ibi e, awon kan gba pe odun 1987 ni won bi.Iṣẹ Lucie koko jade ninu ere “EMojin A Seduireire ni odun 1999 nigba ti Cinema titi Cameroon sese n dagba o di gbajumo ni odun 2008 lehin igbano ni o gba ami eye osere ti o dara julo fun CMAMA Cameroon Movies Merit Award ni odun 2013.. | wikipedia | yo |
O se agbekale ile ise titi eh no, eyi ti o pe ni Lucie Memba Bos (LMB).. | wikipedia | yo |
Ohun lo gbe ere Paradise jade, ise e ninu La Patrie d'abord, je eyi ti oje gbajumo fun gege bi Ẹṣinls ise na, fiimu na ni won fi Pan awon ologun Cameroon le, ni odun 2014 otun bawon se abejade ere "H Nana" eleyi ti ogba Ami eye fun ere Faranse ti o dara julo lowo ECrans Noirs owa lara awon osere ilu Cameroon ti ise won ti di mimo lati ajo asa ati ise ti ilu Cameroon, owa lara awon ti o pade ama tutu eyi ti o se abewo si ibi ti won ti se ere Pintan Poison ni Látinú 2016ani odun 2016 ni ohun ni osere ilu Cameroon ti on dan lati owo lati owo dudu Camerounais otun je gbajumo fun ere fast pelu osere pelu osere okurin ijol.. National lati ohun [ meji awon osere ona ti ise se e ti di Mo d' ijoba lati osere ti ise pelu omo osere lati se ti o pade ni ilu ti ilu osere lati osere ti oko osere lati won se lati se ere ti se Mo yi ni ogba ti se ere osere ni opolopo ona dara julo lati koko lati ohun lati osere lati osere lati se omo se lati orin pelu odun tòsílati won ni ise se omo pelu odun pelu awon ijoba dara lati lati owo se lati o se odun pelu iwe se pelu ere pelu ere ti se ere kan ni omo ona ti o _* | wikipedia | yo |
O sise pelu Tribe Africa Media lati fifehan si awon Afin ni ilu Cameroonyato si ise re ni fiimu, ni odun 2008, Guinness Cameroon gba si ise gegebi olùṣòwò titajaigbesi aye ara eni ni osu Kesan odun 2017, Lucie pade pelu akọọlẹ boolu afẹsẹgba ilu Cameroon Samuel eto'o ni Douwon aṣayan ereodun 2011 si 2017 DeOlùgbọ́ the 6th NTAh Napi de Ousmane Stéphane et Sergio Marcellos Paradise Paradise W.A.A.A.A first country la Maladie Missiondie Missionte Uto Farte Dakore Akande with Akande Pin with àtìpó with Jim Iyke Le Le Blanc d'èyàn a Par'ẹ Ag'abord O'abord Fast 2009 de Gdu his Sweet Home de his àmòú Allah.. | wikipedia | yo |
Com de Serge Ahabujoọdún 2008 Serie Olulanisókè d'Ousmane Stéphane Serie Le Monde dé lọic, De Rpha Matouke virus squàdájíá àti ti ìnilè Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1987Àwọn Ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Adrienne ako anomgbo Koutouan (ti a bi ni odun 1969) je apanilerin ati osere ti o wa lati ilu Côte d'Ivoire.org Koutouan je omo egbe awon eyan Tchaman osi wa lati Abule Abobo-te ni ilu Abobo ti Osun mo Abidjan ati omode ni oti fe je osere, awon obi re o fi gbogbo ara gba ise yi.. | wikipedia | yo |
O bere ise gegebi osere ni awon odun 1980 pelu ere itage "Feweche Eeen" ni odun 1986, won daruko Koutouan gegebi eni ti o mo jo ju ni ile Ivory CoastKouti ti gba ami eye orisiris, bi osere birin ti o dara ju ni ayeye naMur ni ilu Belgium ni odun 1998, osere birin ti odara ju ni ayeye M-Net ni ilu Johannesburg ni odun 1999 ati osere obinrin ti o dara julo ni Africa ni ayeye pabbah ti owaye ni Nàìjíríà ni odun 2006, gba ami eye titi wura ni Panafrican Film and Television Festival ti Ouagadougou fun ipa e ninu reQuand les elephants se inúu.. | wikipedia | yo |
O je gbajumo ni Ivory Coast fun ipa e ninu fut pas fâcher gegebi Rosalie ni odun 2008, Koutouan ko ipa ninu ere Dr.. | wikipedia | yo |
Boris gege bi Infirmière Antoinette pelu Ahmed Souaney.Ni ojo kerinla osu kerin odun 2019, wo ye Koutouan si fun ogbon odun gegebi osere, o gba oriṣi ami eye lati owo ijoba.. | wikipedia | yo |
O de ipo Officer in the order of cultural Merit lati owo ajo asa ati ise .. | wikipedia | yo |
Boris (jara) gegebi Infirmière Antoinetteàwọn itọkasiàwọn ona asopọ ita Adrienne Koutouan at the Internet movie databaseàwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1975.. | wikipedia | yo |
Werewere Liking (ti a bi ni odun 1950, ni ilu Cameroon) je onkowe ati osere ti on gbe ni Abidjan, Côte d'Ivoire.. | wikipedia | yo |
O da egbe ori itage ki-yi mbọ̀ck kale ni odun 1980, osi da Abule Ki-yi kale ni odun 1985 fun eko imo aworan fun awon odo.iwe e elle sera de jaspe et de corail je iwe orin ti o soro nipa MiYíruire nipa kiko iwe iroyin oni ti o da lori nkan mẹsan.. | wikipedia | yo |
Marjolijn De Jager, It shall be of Jasper and Coral; and, Love-across-a-hundred-lives (two novels), University Press of Virginia (2000), La puissance de um (1979) and Une nouvelle Terre (1980) - trans.. | wikipedia | yo |
1991), pp.207–222-222 - accessed at MARCH 1, 2007,Àwọn Àkọsílẹ̀Àwọn ọ̀nà àsopọ̀ ìtaópọ̀ ìta íkò Gdu Ggnepọ̀, University of Western Australia wéréwéré Liking and Aroko of Netoty, postcolonial We ènìyàn Alààyè Ekò Ọjọ́ìbí ni 1950.. | wikipedia | yo |
Yemi Ajibade tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Keje Ọdún 1929.. | wikipedia | yo |
- 24 January 2013), ẹni ti wọ́n mọ̀ sí Yemi Ajibade, Yemi Goodman Ajibade tàbí Adeyemi Ajibade, jẹ́ òṣèré Ori-ìtàgé, Adarí-eré, àti olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó n gbé ní orílẹ̀-èdè England láti ọdún 1950.. | wikipedia | yo |
Ó ti kó ipa ribiribi nínú eré orí-ìtàgé nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pàá pàá jùlọ Canon of Black Drama.. | wikipedia | yo |
Ó ti kọ́ oríṣiríṣi eré, ó sì ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré pẹ̀lú lórí ẹ̀rọgbèwórá, orí rédíò àti sinimá.Ìgbé ayé rẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀=Adéyẹmí Ọláẹ́ Goodman Ajibade ni wọ́n bí ní ìdílé Ọba ní ìlú Ìlá Òràngún ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ tí girama ti ìlú Abeokuta tí ó sì tú kẹ́kọ̀ọ́ nílé Ẹ̀kọ́ Kentonton College of Law and Commerce ní ìlú London ní ọdún 1955.. | wikipedia | yo |
O tun kawe ni ile-ẹkọ ti The Actors' Work ni ọdun 1960, o si tun keko ni London Film School ni odun 1966 ati London School of giMB Technique ni odun.ise re nigba ti o wa ni ilu UK, Ajibade kopa ninu ere ori redio fun ile -ise igbohun-Safe BBC African Service.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa nínu àwọn eré orí-ìtàgé sinimá mìíràn pẹ̀lú.. | wikipedia | yo |
ati ni Lorraine HansBER Les Blancs (Royal Exchange Theatre ní ọdún 2001.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bí Terence Fisher nínú eré The Devil Rone out ní ọdún 1968, gẹ́gẹ́ bí Monte Hellman nínú Shatter ní ọdún 1974 gẹ́gẹ́ bí hánìf Dres nínú eré London kills me ní ọdún 1991 àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Richard èyíMofẹ́ Evans Mofe-Damijo ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1961 ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí RMD, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùkọ̀tàn, agbẹjọ́rò olùgbéré-jáde àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ Komisona fun ati ati Ìgbafẹ́ fun Ipinle Delta nigba kan ri.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2005, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Movie Academy Award fún Best Actor in a leading Role.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ títí làẹ̀ làẹ̀ tí Guwa Africa Movie Academy Awards fún ipa rẹ̀ nínu eré sinimá ní ọdún 2016.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé kò́n bi ríChad ní àdúja Alaja ní ìlú Udu, ìlú tí ó súnmọ́ Warri Koru Koru ní Ìpínlẹ̀ Delta.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Middwest College, ní ìlú Warri, àti ilé-ẹ̀kọ́ ti Anglican Grammar School, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó ma ń ṣeré ìtàgé nígbà náà.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásítì ti uni ben, láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣẹ́ Theatre Arts... | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí Fásitì ti University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ọdún 1997ó ṣe tán ní ọdún 2004.Iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn tí ó jáde ní Fásitì, ó bẹ̀rẹ̀ ère sinimá ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní Ripples.. | wikipedia | yo |
Ṣáájú ítàn á náà, ó ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìwé-ìròyìn Concord àti Metro Magazine.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2005, ó di ìlú mọ̀ọ́ká látàrí Out of Bounds tí ó jẹ́ kó àkàn gidi.Ipa rẹ̀ nínú ìṣèlú wọn yàn Mofẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn pàtàkì lórí àṣà àti ìGBAFẸ́ sí Gómìnà Emmanuel Urokohan ní ọdún 2008, tí ó sì padà di kísọ́nà fún àṣà àti ìfẹ́ fún gbogbo ìpínlẹ̀ Delta ní ọdún 2009 tí ó kúrò ní ọdún 2015 ní ọdún rẹ̀ láfà ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú arábìnrin May Ellen-Ezekiel ti gbogbo èyàn mọ́ sí (mẹ́ẹ̀) tí ó jẹ́ olóòtú àti oníṣẹ́ ìròyìn.. | wikipedia | yo |
Iyawo rẹ yi papòdà ni odun 1996, ti Mofẹ́ si tun se igbeyawo pelu jumọbi AdeGbẹ̀san ti oun je olóòtú eto ori ero amole-máwòrán.. | wikipedia | yo |
Fòpin sí SARS ti gbajumo ògbufọ̀ rẹ lede Gẹẹsi tumọ si End SARS, jẹ́ Ìfẹ̀hónúhàn àwọn òdò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó bẹ̀rẹ̀ lórí Ìtàkùn ayélujára,Twitter láti pe ìjọba àpapọ̀ sí fífòpin sí àkànṣe Ẹ̀ka Ọlọ́pàá Agbóguntolè, Special Anti-Robbery Squ, tí wọ́n fẹ̀fẹ̀ sílẹ̀, tí wọ́n wá ń pa làpálàpá nípa Híhalẹ̀ mọ́ àwọn aláìṣẹ̀ àti gbígbógun ti àwọn ará ìlú lọ́nà tó lòdì sí òfin.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ náà bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpolongo lórí ìkànnì ayélujára Twitter pẹ̀lú aroko ▪End láti sọ fún ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti fòpin sí àkànṣe ẹka Ọlọ́pàá Agbógun AgbógunRAtólẹ̀, SARS.. | wikipedia | yo |
Láàárín òpin ọ̀sẹ̀ kan, lọ́jọ́ kẹsàn-án sí kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 2020, (9-11 October 2020), àrokò #EndSARS ti ní ìpolongo mílíọ̀nù méjìdínlọ́gbọ̀n lórí Twitter.. | wikipedia | yo |
A lè rí àwọn fídíò-bọ̀ṣẹ̀ lórí ìkànnì ayélujára yìí EndSARS wọ́n fẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá SARS pe, iṣẹ́ ni wọ́n dàmú àwọn aráàlú nípa ṣíṣe fín ìgbónára àìtọ́ fún aráàlú, jíjínigbé, ìpànìyàn, jídún, olè, ọ̀lẹ, ìfìyàjẹ aláìṣẹ̀ lọ́nà àìtọ́, títí aláìṣẹ̀ mọ́lẹ̀, pípayàn lọ́nà àìtọ́, ìfipágbọ́wọ́ àbẹ̀tẹ́lẹ̀, híhalẹ̀ àti gbígba owó lọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n bá rí nínú ọkọ̀-ayọ́kẹ́lẹ́ bọ̀gìnnì, ìdásílẹ̀ ibùdó àyẹ̀wò àìtọ́, àyẹ̀wò ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, pàápàá jù lọ IPnesnes.. | wikipedia | yo |
Àwọn kan kéde pé ìfẹ̀hónúhàn náà ti ṣe àṣeyọrí nígbà tí àwọn aláṣẹ ọlọ́pàá kéde pé wọ́n ti fòpin sí àkànṣe ẹ̀ka ọlọ́pàá SARS lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Àwọn mìíràn tako èyí, wọ́n sọ pé ìjọba ti ṣe irú ìlérí bẹ́ẹ̀ rí ṣùgbọ́n tó jásí pàbó, tàbí tó jẹ́ pé pàbó ló jásí.. | wikipedia | yo |
ìjọba ti gbìyànjú láti fipá dá ìfẹ̀hónúhàn náà dúró, ṣùgbọ́n pàbó ni gbogbo ìgbìyànjú wọn n ja si.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Sola fóṣùdo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1958, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé oun sinimá, ọ̀mọ̀wé,aláriwoye àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ kòpò bi Sola ní Ìpínlẹ̀ Èkó, , ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ eré oníṣe láti ilé-ẹ̀kọ́ Obafemi Awolowo University àti University of Ibadan, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìkejì nínú ìmọ̀ eré oníse.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu eré sinimá oríṣiríṣi tí ó sì tún ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Níkè okùn.Òun ni adarí àgbà fún ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Theatre Art ní ilé-ẹ̀kọ́ ti Lagos State University.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ True Confession Glamour girls iriranals Strange Ordefara AlhajiFamily on Fire (2011)Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ládédédé ní 1960 ní 1960 Alààyè Alààyè Film Actors Àjàpá lá Actors lati People Stubs of Birth Missing (Living People)male of Yoruba Cinev Gov State Faculty 2008-21st Nigerian Mago Actors from lati Lagos State of Ibadan of Ibadan Awólọ́wọ̀ University alu Acadéckout Acadéckout.. | wikipedia | yo |
Irene Tassed (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kejo odun 1956) je onijo, akorin ati osere ti o wa lati orile ede Burkina Faso.org o ko ijo ibile titi Ouagadougou, lehin na o ko ijo imusin titi ile Europe, lehin Germaine Agàǹgàny, ni ile iwe Mudra Afrique, ti Maurice Bejart da sile ni Dakar bBNxnxnmxnmxmmxmx,mxmlẹhìn idanileko yi, o ko lo si ilu Europe gegebi onijo, ni awon odun ibẹrẹ ti 1980,.. | wikipedia | yo |
O man lo si ilu Burkina Faso Dada, ati pe o ti se orisisi Iroko ni orile ede orilẹ-ede Iṣọkan Awọn Ipinle Amẹrika ati ni Europe.. | wikipedia | yo |
Ni odun 1988 o da Comgnie ébène ni ilu Parisi, eleyi ni o fi se irin ajo lo si ilu orisirisi lati fi ise e gege bi olorin fi han si awon eyan.. | wikipedia | yo |
O Ditan, o si tun ririn ajo pelu egbe Fusion ni odun 1988, ni odun 1989 o rin irin ajo pelu egbe Diamiïx.. | wikipedia | yo |
O ko ipa ninu ipade Caravane d'Afrique Francophone ti o waye ni ilu Paris, ni ọdun 1991.. | wikipedia | yo |
O bere Surnga ni ìlú Paris, ní osù kewa odun 1992 bbbbbb odun 1993, ohun ati egbe e ririn ajo wa si ipele akoko titi aworan ile Afrika ati idani laraya ti o wáàyè ni ilu Abidjan.. | wikipedia | yo |
O di gbajumọ wọn si yan fun Ijo ti o ma n waye ni ọdọdún meji ti ti Lyon, ni ọdun 1994, okiki rẹ gegebi akorin ati oni ijo tan kakiri.. | wikipedia | yo |
O tun sise pelu ile abinibi e, lehin igba ti won da ajo onijo Ballet titi Burkina Faso kale.. | wikipedia | yo |
A ko awon onijo lati origun Burkina, gbogbo won ko ijo ti won mo tele."Awon itọkasi awon eniyan apapoawon Ọjọ́ìbí ni 1956.. | wikipedia | yo |
Dakore Egbuson-Akande (ti oruko re tele n je Dakore OmoBola Egbuson) je osere Nigeria.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ aṣojú fún Amnesty Internation, Amstel Malta àti OXFAM ni America.ìgbésíayé ìpínlẹ̀ Bàtata ni wọ́n bí Dakore sí, gẹ́gẹ́ bíi àkọ́bí àwọn òbí rẹ.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ìwé Corona àti ilé-ìwé ìjọba àpapọ̀ fún àwọn ọmọ obìnrin ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó kọ́ ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀ ní Fásitì Èkó ṣùgbọ́n kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nítorí Ìgbélé gbogbo ìgbà Ó ti ṣe ìgbéyàwó báyìí, ó sì ti bí ọmọ méjì ní Oṣù-án Ọdún 2019, wọ́n ṣe àfihàn daé nínúe nínú ìwé Àwòrán ti Visual Collaborative, nínú ìpele tí wọ́n pè ní Vivencias tí ó "Ìrírí" ní Èdè Sìńì.. | wikipedia | yo |
Fatoumata Coulibaly je osere fiimu ara ilu Mali adari, akoroyin, ati ajafeto eto awon obinrin, ni pataki julo ko gba di da abe fun awon ọmọbirin.igbesi aye ibere Fatoumata Coulibaly wa lati ebi awon olorin, iya-iya e Bazeko Traoré je olorin lati apa Sikas, ibi ti Coulibaly ti Wa.Coulibaly koko sise gegebi akoroyin redio ati Olùkede ni Mali, ki o to ri imoran fun ere kan, lehin ti o ri imoran na olori oludari Ousmane Sow, Sow so fun pe ki olo ko kale gege bi iwe fiimu, Cheik Oumar Sissoko na so nkan kana fun.Coulibaly koko fa ifojusi kariaye pelu ipa re ninu fiimu 1997 N'oloolo Dit papa.. | wikipedia | yo |
Coulibaly ko ipa iwaju ninu fiimu odun 2004 kan ti akole re je Moofàsí, omo ilu Senegal kan ni o ko ere na, Ousmane Sembène lo dari e.. | wikipedia | yo |
Coulibaly ko ipa Colle Gallo Ardo sy, iyawo keji ninu meta tí ọkọ ẹ̀ fẹ́, ní abúlé kan ní Burkina Faso, ó man fií agbára idán tí Moobọ́ọ̀lù ni láti fi kó àwọn ọmọ obìnrin yọ ninu ìdábẹ́.. | wikipedia | yo |
Coulibaly na je okan lara awon omo obinrin ti won Dabe fun.. | wikipedia | yo |
Roger Robert fun ere na ni irawo mẹrin ninu mẹrin, ó ní fún ohun ère ti odara ju lo ni Cannes ti odun 2004 ni ere na, ó ni ere na ni agbára ti ó pò, àti pé oni awon nkan ti o pani lerin ninu, aworan e si dara gidi gan, ko da orewa.. | wikipedia | yo |
Coulibaly gba ami eye osere ti odara ju lo fun ipa e gege bi Colle ni ami eye CineManila ni odun 2005.. | wikipedia | yo |
Ni odun 2016, Coulibaly sise pelu office de radiodiffusion télévision du Mali.. | wikipedia | yo |
Openiyi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kẹfà ọdún 1988, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti àti sinimá ọmọ Oìlú-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
òun ni gbogbo ènìyàn mo sì tsh látàrí ipá rẹ̀ tí.Ó kó nínú eré 'The Hunger Gamesoṣù | wikipedia | yo |
òun náà tún ní ẹ̀dá ìtàn and Danny Dyson nínú eré Terminator Genisys.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀wọn bí Dayọ̀ ní ìpínlẹ̀ Jóṣ Lóotọ́, àmọ́ ó dàgbà sí ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú àwọn àbúrò mẹ́rin lẹ́yìn rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì láti ilé-iṣẹ́ aṣọ́bodè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ tí ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ Lítíréṣọ̀ láti orílẹ̀-èdè Kenya.Òun àti àwọn ẹbí rẹ̀ kó kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ sí ìlú Indiana ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, kí wọ́n tún tó kó lọ sí California ní orílẹ̀-èdè.Amẹ́ríkà Bákan náà. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ gboye akọkọ ninu imo Visual Communications ni Ile-ẹkọ Anderson University (Indiana) ni ọdun 2009.ṣaaju ki o to kopa ninu ere The Hunger Games, Okeniyi ti sise ni awon sinima ese-kuku ati yiya Ere itage.. | wikipedia | yo |
ó sì tún ti kópa nínú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan eré NBC bíi Shades of Blue.Àwọn Aṣayan fíìmù rẹ̀àwọn àmì-ẹ̀yẹ Acdi2013 Nigeria Entertainment Awards - Best International Actorawọn Ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn ìjásóde Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1988-21st American Maight Actorsa Mata film Actorsa People People of Yorùbá descentan University (Indiana) Aluпо ènìyàn Asgunmale From Cali Califor Àjàpá from Indianamale from Actors from Lagos Grants to the United StatesYorùbá Àjàpá Actors | wikipedia | yo |
àfẹ́àfẹ́z Oyetoro ti won bi ni ogunjo osu kejo odun 1963, je Aderin-pọ̀pọ̀, osere sinima ati omowe omo orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oun ni gbogbo eniyan mo si "Saka".ÌBẸ̀RẸ̀ aye ati eto Eko rẹwọn bi àfẹ́èṣìz ni Ilu ìsẹ̀yín ni Ipinle Oyo ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ àti ẹ̀kejì nínú ìmọ̀ Theatre Art láti ilé-ẹ̀kọ́ Obafemi Awolowo University àti University of Ibadan.. | wikipedia | yo |
Ó sì ń kẹ́kọ̀ọ́ sí.lówó láti gba oyè ọ̀mọ̀wé ní Fásitì ìlú Ìbàdàn lọ́wọ́.Iṣẹ́ reafèéz di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó ma ń kó nínú eré gẹ́gẹ́ bí aláwàdà àti Adérìn-pọ̀pọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríàó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ eré oníṣe nílé ẹ̀kọ́ olùkọ́ ti Adéníran Ògúnsànyà College of Education tí ó wà ní ìpín ìpínlẹ̀ Èkó.Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùpolówó fún MTN ní ọdún 2013 tí gbólóhùn rẹ̀ yí "i Don Port ó.” sì gba ìgboro kan.. | wikipedia | yo |
i ọdún 2016, ó kópa nínú eré The Wedding Party àti nínú eré aláwàdà ti Ojúkòkòrò (Greed).Ìgbé ayé reafèéz gbé aya rẹ̀ Ọládé Oyètoro Kópókú, wọ́n bímọ ọkùrin méjì Abdullahi Oyetoro àti múnim Oyántoro àti ọmọ obìnrin kan ṣoṣo Rufiat Oyetoro.Àwọn fíìmù tí ó ti.kópa ní ojúkòkòrò (2016)The Wedding Party (2016)The Wedding Party 2 (2017) Chops (2020) alsoLISER of Yoruba People Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè Ọjọ́ìbí ní 1963 Ma Àjàpá Àjàpá film Actors Actors From Oyo Stata Stagg Meâs Actors in Yoruba Cinls Cocean Femi Awodie Shutime of Ibadan of Ibadan Acadéagolo Acadéckout.. | wikipedia | yo |
Fatoumata Diawara (ti won bi ni odun un 1982 ni Ivory Coast) je osere, olorin ati ako-orin, ti a ti yan lopolopo igba fun ami-eye Grammy Award.. | wikipedia | yo |
wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ lẹ́ẹ̀méjì fún Grammy Award titi ọgọ́talelọ́kàn fún Awo orin Àgbáyé tí ó dá jù fún àwo orin rẹ̀ Fenfo àti fún orin ijó tí ó dára jù nípasẹ̀, Ultimatum eléyìí ti Disclosure gbà lalejo lórí orin náàìgbésíayé ìlú Ivory Coast ní own bi Diawara si fun awon obi ti o wá láti Mali.. | wikipedia | yo |
Ni asiko odo e, won mu pada losi Bamako ni Mali, ki o lo ma gbe lọ́dà anti re.. | wikipedia | yo |
Ni igba ti o pe ọmọ ọdun mejidinlogun o ko lọ si ilu France lati lọ ma se iṣẹ osere.. | wikipedia | yo |
Ó pàdí sí Mali fún ìgbà díẹ̀ fún ipa kan nínu eré, ṣùgbọ́n ó padà sí Paris lesekese, nítorí kò fẹ́ kí wọ́n fipá mú lọ sí ilẹ̀ oko.Ni gba ti oya, Diawara pada mu jita, osi bere si ni ko awon orin titi e, àwọn orin tí ó ní àwọn asa Wassoulou ti apa guusu Mali, pelu awon ipa agbaye ninu orin e.Fiimu ati ere itage lehin igba ti o ko lo si France, o ko ipa ninu ere Cheik Oumar Sissoko ti o se ni odun 1999 ti akori re je Genesis, Dani Kouyate, ni odun 2001 ó ko ipa ninu ere Sia, le reve du python ati egbe ere itage ti Royal de Luxe.. | wikipedia | yo |
O tun ko ipa ninu ere olorin ti akole re je Kirikou et Karaba.Nigbakanna bi o sen korin, ni o n se ere ori itage na, pelu orisirisi ipa pelu orisirisi ere otun ko orin fun orisiris ere bi Tim, ere yi gba ami eye César meje ati yiyan lati owo Academy Award ni odun 2014o je gbajumo fun ohun aladun ede Bambara ni oma fin korin, ede yi je ede abinibi ti Mali, orin e Sima da lori Iyen níyànjú bi asa titi awon Wassoulou Diawara ti korin pelu awon omo orile ede Mali ati awon olorin agbaye bi Cheik Aaneane Seck, Oumou tìnku, Afrobism, dèé dee Bridgewater , ati The Orchestre Poly rymo de de Cotonou.. | wikipedia | yo |
Awo orin e Kanou jade ni ojo kesan osu karun odun 2011.. | wikipedia | yo |
Àwọn orin e Alakoko ti o fi lole, Fatou láti ọwọ́ World Circuit Records ni osu Kesan odun 2011 Nonẹ̀ṣùch Records fi Kanou EP kale ni Ori ayelujara ni Ariwa Amẹ́ríkà ni ojo ketadinlogbon osu Kesan odun 2011 won si fi awon orin Miran ni ojo kejidinlogbon osu kejo odun 2012.Ni osu Kesan odun 2012, Diawara ninu ipolongo ti akori e je “30 Songs / 30 Days" lati fi fun half the Sky ni ati leyin, eleyi je ise agbase media to po ti o waye nipasẹ iwe Sheryl wuDunn ati Nicholas Kristof kan na ni osu Kesan odun 2012, o wa lori eto African Express Train pelu àwọ eyan bi damọn Alfn, Rokia, Kakoko Traoré, el, Amadou & Mariam, Nicolas Jaar ati awon noisettes, ati bebe lo.. | wikipedia | yo |
Eto na gba alejo awon eyan ẹgbaaji o le ẹdẹgbẹta ni Kings Cross ibi ti Fatoumata ti korin pelu Paul McCartney.Diawara ti lo awon odun yi lati fe sere kakiri agbaye,ni ajọdun yẹ̀tonbury titi odun 2013, Fatoumata ko orin fun awon eledi geesi, ere ojo na dun yato.. | wikipedia | yo |
Yato fun awon ere orin Europe won ti pe ki o wa korin ni guusu Amerika, Asia ati Australia,oti lo si ilu Amerika lopolopo igba, ni odun 2013 o sere fun won ni Clinton Global Initiative legbe The Roots ni Ilu New York lati arin odun 2014 ni oti ba opolopo awon osere korin, awon osere bi Roberto ti won ti won ti jo se opolopo orin kiko ori itage ati awo orin ti ori itage ti akori e je At Home - Live in Marciac.. | wikipedia | yo |
Ni odun 2014 o korin pelu Mayra Andrade ati Omara PortuOǹdó.. | wikipedia | yo |