cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Lẹhin igba na o bẹrẹ iṣẹ pẹlu ile ise telifisonu Wbs fun awon ewe, o se eto yi fun odun mẹrin pelu awon ewe miran.Ni odun 2010 ati 2012 o se adari eto K-Files..
wikipedia
yo
Wọ́n gbẹ́ sórí afẹ́fẹ́ ní NTV(Uganda) àti ITV àti sọ́bíàn titi ìlú Kenya..
wikipedia
yo
O se oludari Big Brother Africa ni odun 2012.Flavia Mock NTV Uganda gegebi adari iroyin lorin NTV Toñight ni odun 2016..
wikipedia
yo
O wa lara awon oludari eto aro kan lori NTV ti o bere ni odun 2018.Redio Tumusiime se ise gegebi adari eto lori ikani HOT 100 FM ni odun 2006 ki oto wa pada si Capital FM ibi ti owa disinyi.Awon ami eye ami eye fun àwọram ati iroyin titi Young Achievers Award ami eye fadaka fun eto aro ti odara julo ni Radio and TV Awards ti odun 2013.
wikipedia
yo
Ami eye eni awokose fun awon odo ti Buzz téènì Awards odun 2013.
wikipedia
yo
Òṣìṣẹ́ MÍDÍÀ tí ó mọ́ ara mú jù lọ ní ọdún 2015 ní Abryanz Style and Fashion Awards òṣìṣẹ́ rédíò obìnrin tí ó dára jùlọ - Uganda Entertainment Awards ní ọdún 2016àwọn èyàn eréfíìmùàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1988..
wikipedia
yo
Ilé ifẹhinti lẹ́nu iṣẹ́ tàbí ilé ifẹhinti lẹ́nu iṣẹ́ – nígbàkan tí a pè ní ilé lrẹ̀ẹ́ tàbí ilé ifẹhinti kan – Bótilẹ̀jẹ́pé ọ̀rọ̀ yìí tún lè tọ́ka sí ilé ńtọ́jú kan – jẹ́ ilé-gbígbé ibùgbé púpọ̀ tí a pinnu fún àwọn ènìyàn àgbàlagbà..
wikipedia
yo
Nigbagbogbo, gbogbo eniyan tabi tọkọtaya ni ile ni yàrá kan ti o jọra si ìyẹ̀wù tabi ìyẹ̀wù ti àwọn yàrá..
wikipedia
yo
Eyi le pẹlu awọn ohun elo fun awọn ounjẹ, awọn apejọ, awọn iṣẹ ere idaraya, ati diẹ ninu iru ilera tabi alejo..
wikipedia
yo
[3] Ibi kan ni ilẹ̀ ifẹhinti lẹ́nu iṣẹ́ lé ṣẹ̀ẹ́ san lori ipilẹṣẹ yíyalọ kan, gẹ́gẹ́ bí ìyẹ̀wù kan, tàbí o le ra nigbagbogbo lori ipilẹ kanna bi ilé gbigbe kan..
wikipedia
yo
[4] Ile ifẹhinti ṣe iyatọ si ile ńtọ́jú ní akọkọ ni ipele ti itọju iṣoogun ti a pese..
wikipedia
yo
Ìmúṣẹ gbogbo àwọn ìfẹ́kùfẹ́ wọn.4– Àyíká ìléra bí a ti mẹ́nuba tẹ́lẹ̀, a gbọ́dọ̀ pèsè ìtọ́jú ìléra fún wọn àyíká tí ó bálò láìsí àwọn eewú àti gbogbo àwọn orísun tí ìdọ̀tì àti Ariwo tún jẹ́ pàtàkì, nítorí àwọn ara wọn àti àwọn ètò mímú kó ru àwọn ìgárá wọ̀nyí.Ìmọ̀ràn fún àwọn àgbàlagbà nílò ìgbìyànjú púpọ̀, nítorínáà ènìyàn ìmọ̀e kan gbọ́dọ̀ wà tí ó tẹtisi wọn, ẹnití ó súnmọ́ wọn, tí ó lóye wọn tí ó sì ní ìtara fún wọn, àti pé yóò jẹ́ ìrànlọ́wọ́ àti àtìlẹ́yìn fún wọn...
wikipedia
yo
Fatiha Berber (odun 1945 titidi odun 2015) je ẹ̀ṣẹ̀rẹ̀ omo ilu Algeria ti atun mosi Fatiha Blal.ìgbésíayé a bi Fatiha Berber ni Casbah of Algiers..
wikipedia
yo
A won molebi re wa lati Legata ni Boumerdes Province titi apa ariwa ilu Algeria.Ni odun 1950 ọ̀kọ pelu awon Meriem Fekka, lehin igba na olo ko eko drama ni Conservatory of Algiers..
wikipedia
yo
Oludari Mustapha Gribi fun ni ipa e akoko ninu ere Molière, Les femmes savantes..
wikipedia
yo
Ọkọ ipa ninu Algeria's National Liberation struggle.O se alaisi ni ojo kerindinlogun osu kini ni odun 2015 ni pa se arun okan.Awon iseawon fiimu Hassan Taxi, Dir..
wikipedia
yo
Amar Tribeche, 1990 Le Peto au Femited [Woman as The Devil], Dir..
wikipedia
yo
Thomas Glou, 1995 Prima del Tramọnto [before Sunset], Dir..
wikipedia
yo
Karin AlBou, 1999tẹlifisiọnu jara el Olumásì [Destiny] el La'IBM [The Player], 2004 el Biya [The Yâria], 2008-10Àwọn Ìtọ́kasí Awọn Ojoaláìsí ní 2015Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1945..
wikipedia
yo
Malika Belbey (ti abi ni ojo kẹdogun osu kefa odun 1974) je osere ti o wa lati ilu Algeriaìgbésíayé ilu Ti’ ni won bi Belbey si, ni apa iwo Oorun titi Algeria.O lo si Algiers School of Dramatic arts..
wikipedia
yo
Belbey bere ise osere pelu ere ori itage ti akori re je ''Nene’’ma ti won mu lati iwe ti Kateb Yine ko, ti Zani Cherif Ayad se oludari e..
wikipedia
yo
O se igbaibajade telifisonu ni odun 2004 pelu,The Player..
wikipedia
yo
O wo inú àjọ cinema pẹ̀lú Barakat! Ní ọdún 2007, ó kópa nínú fiimu Morituri , eleyi ti oda lórí iwe ti Yasmina Khadrako
wikipedia
yo
Ìwé aṣaragágá na dá lórí Ọlọpa ti ó ṣe iwadi àwọn ẹgbẹ́ apániláyà kà ni àsikò ogun Algerian Civil War..
wikipedia
yo
Belbey kopa ninu jara telifisonu Djemai Family ni odun 2008..
wikipedia
yo
O kopa ninu Dayok el Akhira ni odun 2010 ati 2011.Ni osu keta odun 2014 won se ike fun ni 13th Gulf Radio and TV Festival ni Bahrain.Ni odun 2019 o ko ipa meji ọtọtọ ninu ere ti Sawo Hamdi se, ti osi pe akori re ni Reconnaissance..
wikipedia
yo
O gba ami eye oṣere obinrin ti odara ni Maighreb Film Festival ni Ougbédègbẹ́yọ̀, Morocco..
wikipedia
yo
Belbey kopa ninu jara TV ti odun 2020 ti akori e je maakati..
wikipedia
yo
O ni ipa ti ohun ko, jẹ ipa obinrin ti oti je iya lopolopo, sugbon otun ile e ko lai biki fun odun mewa to lo ni ẹ̀wọ̀n..
wikipedia
yo
Lehin igba ti oka ipa yi , Belbey ofe ko iru ipa ti oko tele ri ninu jara imiran..
wikipedia
yo
Tóyìn Adélálá ti gbogbo ènìyàn mo sì aṣẹ́wó tó rẹ Mẹ́kà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1961..
wikipedia
yo
ó jẹ́ òṣèré sinimá Yorùbá, olùgbéré-jáde àti adarí eré Ọmọ.orílẹ̀-èdè Nàìjíríàiṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimáó bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé Yorùbá Ní ọdún 1984, Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ Amúṣẹ́ṣe Arts and Culture Council, Ẹ̀ka ti ][Ìpínlẹ̀ Osun]].igbe ayé rẹ̀Tóyìn ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Oṣeré oníṣẹ́ ìròyìn kan tí ó ti di olóògbé..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì tí ọ̀run fi jíǹkí rẹ̀ ni wọ́n ń gbé ní orílẹ̀-èdè Dublin àti Ireland , bákan náà ni ó tún ti ni ọmọ-ọmọ.Lára àwọn eré rẹ̀ niaṣẹ́wó tó rẹ Mẹ́kà (1992)Nàìjíríà (2013)àwọn ìtọ́ka Ganig Film Actresṣe ènìyàn Amíràn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1961Nigerian Film People Actdàti in Yorùbá Cinemáact From Osun Nigerian20th-Century Nigerian Actresses-Century Nigerian Actresses ;
wikipedia
yo
Fisáyọ̀ Ajisola, tí gbogbo ènìyàn tún mọ́ sí FreeZon,jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ṣeré ìtàgé, Model àti akọrin..
wikipedia
yo
Ó di ìlú mọ̀ọ́ká látàrí ipa tí ó kó nínú eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ Jenifa's Diary, pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé..
wikipedia
yo
Ó tún ma ń kópa nínú eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ This Life, Netitar, Shadows, Burning spear, Circle of interest àti the story of Us ní orí èrò amóhùmáwòrán-máwòrán..
wikipedia
yo
Ó keko gboye àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Biochemistry lati ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Agriculture, Abeokuta (FUNAAB), ní ìpínlẹ̀ Ogun.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹwọn bí FIsáyọ̀ ní ìlú Èkó, àmọ́ ọmọ bíbí ìlú Ahabu ní ìpínlẹ̀ Ekiti ni àwọn òbí rẹ̀..
wikipedia
yo
Òun sì ni àbíkẹ́yìn àwọn ọmọ mẹ́tin tí àwọn òbí rẹ̀ bí.Fisáyọ̀ bẹ̀rẹ̀ eré-ìtàgé láti ìgbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama Federal Government College (FGc) Odòtabirimoni, ní ìpínlẹ̀ Ògùn ..
wikipedia
yo
ó dara pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́ni ní eré ìtàgé ti Wale Adénúga ( Pef School) ní inú ọ̀sẹ̀ keje ọdún 2010, níbi tí ó ti kọ́ nípa eré orí-ìtàgé.eré tí ó kọ́kọ́ kọ́kọ́ di ìlú mọ̀ọ́ká ní nnena and Friends show, nínú ọ̀sẹ̀ kẹjọ ọdún 2010..
wikipedia
yo
Ó sinmi díẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ fúngbà díẹ̀ láti lè gbájú mọ́ ẹ̀kọ́ nígbà tí ó wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
O bẹrẹ.si n gbe ere tirẹ na .jade ni ọdun 2016, nigba ti o kọkọ gbe ere sinima bi Road to Oruin, pẹlu iranlọwọ aj9 rẹ ti o da silẹ..
wikipedia
yo
Ó gbé eré yí jáde láti le ta ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jí kí Eọ̀n lè má pèsè iṣẹ́ gidi fún àwọn ọ̀dọ́ langba tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ gbogbo.àwọn eré àgbéléwò rẹ̀eré Susdoàwọn Ìtọ́kasí-21st Nigerian Actresses Female Model Model Ènìyàn Alààyèdó From Lagos Actresses Film Actresses Act, Television Act University of Agriculture, Abeokuta AluFederal Government College, Odogbolu Aluniye of Birth Missing (Living People)..
wikipedia
yo
Sandra Prinsloo (Bii ni ojo keedugun osu Kesan-an odun 1947) ti awon eeyan tun ma n pe ni Sandra Prinlowlow je osere ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ipa Kate Thompson tí ó kó nínu eré The Gods must Be Crazy ní ọdún 1980.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Prinsloo sọ wí pé òun kò lérò pé òun ma jẹ́ òṣèré..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó gba ẹ̀bùn Order of ÌKhaman láti ọ̀dọ ìjọba South Áfríkà fún àwọn iṣẹ́ rìbìtì tí ó ti ṣe.ní ọdún 2018, ó gba àmì ẹ̀yẹ Lifetime Achievement Achievement Awards láti ọ̀dọ nálẹ̀dí Theatre Awards.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nhathi Moshesh(bíi ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹjọ Ọdún 1969) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Supporting Role ní ọdún 2016ise nthathihi ti kópa nínú àwọn eré bíi Solun soldier, home Affairs àti Human Cargo..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó darapọ̀ mọ́ àwọn òṣèré fún eré Saint and Sinners Soap..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015 ó kópa nínu eré Ayanda tí wọ́n sì ṣe ìfihàn rẹ̀ ayẹyẹ Durban International Film Festival..
wikipedia
yo
Ipa rẹ̀ nínu eré yí lọ fàá tí wọ́n fi yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ ti òṣèré bìnrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Africa Movie Academy Award..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2016, o gba ami eye gege bi osere binrin to dara ju lo lati odo South African Film and Television Awards.leyin iku osere Mary Makgatho, Nhathihi soro nipa ise rìbìtì ti osere na se ki o to ku.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Florence Masebẹ̀ (bíi ní ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kọkànlá ọdún 1972) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ ède South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré MuvMaro..
wikipedia
yo
O gba ami eye oṣere binrin to dara ju lati ọdọ Africa Movie Award nibi ayẹyẹ Kesan-an ti African Movie Academy Awards.Àṣàyàn àwọn eré tí o ti ṣe Morwale Morla 7 de Laan Afrikaans scandal Force Force Soul City Eleent Ring of liesàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Nousamo Nxumalo Mbatha (Bii ni ojo ketala osu keje odun 1990) je osere, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, ọlọ́jà ati Aoriri ni orile ede South Afrika.ibẹrẹ pepe aye rẹ won bii ni ojo ketala osu keje odun 1990 si ilu Kwas..
wikipedia
yo
O lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ti Ripples Primary School ní Durban àti Bechet High School..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó gboyè jáde nínú ìmọ̀ ìṣirò owó láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Cape Town.Isẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe pẹ̀lú eré Isibáyà..
wikipedia
yo
O ṣe atọ́kùn fun eto káwọn Swap ni ọdun 2014 lori South African Broadcasting Corporation..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ilé iṣẹ́ Okáyà Digital Media ni pé ó wà láàrin àwọn ókáyà Rẹ̀ 100 Women Honorees..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán fún African Movie Academy Awards gẹ́gẹ́ bíi òṣèré tó dára jù lọ fún ipa mọ́ratíwá tí ó kó nínu eré Tell Me Sweet Something ní ọdún 2015.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Thkin Mbenben (Bii ni ojo kejo osu keje odun 1991) je osere lórílẹ̀ ede South Afrika..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Emmy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré Is'Thunzi...
wikipedia
yo
Ó kó ipa Kitso Medúpẹ́ nínú ère scandal!, Nosísá nínú eré Isibáyà àti boni Khumalo nínú ère Saints and Sinners...
wikipedia
yo
Wọ́n bíi Thusọ sí ìlú Pelham ní ilẹ̀ KwasZulu-Natal, ibẹ̀ sì ni ó dàgbà sí..
wikipedia
yo
Iya baba rẹ ni o tọju rẹ titi o fi dagba nitori pe awọn obi rẹ ku nigba ti o wa ni ọmọde..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Wsttutù níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ physical Theatre and Performing Arts Management..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó lọ sí Stella Adler Studio Acting ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Ní ọdún 2014, ó kópa ní ránpẹ́ nini eré Isibáyà kí ó tó wá padà sínú eré Scants.So bẹ̀rẹ̀ eré orí Oriwe nínú eré Is'Thun ní Oṣù Kẹwàá ọdún 2016, ó sì kó ipa Winnie nínu eré náà..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kesàn-án ọdún 2017, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ti International Emmy Award fún òṣèré bìnrin tó tayọ jùlọ fún ipa Winnie tí ó kó nínú eré Is'Thun.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Bonnie Mmbuli (Bii ni ojo keta osu keta odun 1979) je osere, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati ira ni orile ede South Afrika.O se atọkun fun eto AfAfAf Express..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, ó kó ipa Jasmine Hadley nínu eré nought and Crosses tí BBC gbé jáde.ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí sí ìlú Sòwẹ́tò ní orílẹ̀ ède South Áfríkà ní ọdún 1979..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Dominican Convent School àti Greenside High School ní ìlú Johannesburg..
wikipedia
yo
Oun ni akobi laarin awon omo meta ti awon obi re bi.ise o bere si ni se ere nigba ti o wa ni omo odun Me, o si kopa ninu ere Viva Families ni odun 1992.Àṣàyàn awon ere re In113 (2009) Catch a Fire (2006) drum (2004) Gaz'L (13 (13 episodes, 2003-2004) Traffic!12 February (2014)igbe aye re mbu Fel osere ati agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti oruko re je ṣiṣan ipinlenana, won si ni omo meji..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n pínyà, ó kọ ìwé ìtàn nípa ayé rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sophie Lichaba (bíi ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹfà Ọdún 1973), jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà.Èkó Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ní Zimbabwe, ìyá rẹ̀ gbé lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn aláìbi ìyá kí ó bá lé ní Èkó gidi..
wikipedia
yo
Jessica Ayanda Nkoyo (bíi ní Ọjó Ogun Oṣù Kìíní Ọdún 1990) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní orílẹ̀ èdè South Afrika.Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹpẹ ayé rẹ̀ wọ́n bí Jessica sí ìlú Empangeni..
wikipedia
yo
Ni igba ti o pe omo odun mokanla, baba re di alaisi.O lo si ile eko giga ti University of KwasZulu-Natal, o si gboye ninu ere sise ni odun 2012.Iṣẹ ni odun 2013, nkosi bere ere sise, o ko ipa Qônsile ninu ere Isibáyà, ere naa si lo je ko di gbajumo..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó ṣe Eve nínu eré ayẹyẹ.Ní ọdún 2017, ó ṣe atọ́kùn fún ètò A-list èyí tí bet gbé kalẹ̀..
wikipedia
yo
O ṣe atọ́kùn fun eto our Perfect Wedding.O jẹ Ambadodo fun Ile Ise Duran Tourism, Clíque ati Volvo.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Damilola Adegbitẹ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù karùún Ọdún 1985 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amolò-máwòrán àti Model..
wikipedia
yo
Ó kópa gẹ́gẹ́ bi 'Thetẹ̀wé Duke nínu eré onigba-dègbà ti Tinsel, àti gẹ̀gẹ̀ bi ẹ̀mí Williams nínú eré flower Girl..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèré binrin tí ó peregedé jùlọ fún àwọn eré alátìgbà-dègbà ti 2011 Nigeria Entertainment Awards.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé kòpò bi Damilola ní ìlú Sùúrùlérè ní Ìpínlẹ̀ Èkó }..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Queen's College ní ìlú in Yábàá ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Bowen University ní in ìlú Ìwó ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun..
wikipedia
yo
Femi tun n kopa ninu ipolowo ọja ọlọkàn-o-jọkan.Isẹ̀mí rẹni inu oṣu kejo ọdun 2014, Damilola di ololufẹ oṣere kan Chris Attoh, ti won jo n kopa ninu ere Tinsel..
wikipedia
yo
Wọ́n bímọ ní inú ọdún oṣù kẹ́sàán ọdún 2014 KQQn náà tí wọ́n sì sọ orúkọ ọmọ náà ní Brian..
wikipedia
yo
Adegbitẹ àti Atr ṣe ìgbéyàwó bòńkẹ́lẹ́ ní ìlú Accra, tí ó jẹ́ olú-ìlú Ghana ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kejì ọdún 2.2015.ní inú Oṣù kọkànlá ọdún 2017, ìròyìn gbòde wípé ìgbéyàwó Adegbitẹ àti Attoh ti forí sopọn..
wikipedia
yo
Tunde Aladese jẹ Olukọ̀tàn ti o si tun ti gba ami-eye ti Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Leading Role ni ọdun 2018.O ti kọ itan ti a 70 Night Drama fun MTV Shuga filmed by the Actors Agbawọle Over Four Countries, explaining and Set during the coronavirus Lockdown .ise Redese ti nifẹ si ere ori-itage lati igba ti o ti wa ni ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nibi ti o ti dara pọ̀ mọ́ àwùjọ ẹgbẹ́ osere ti o si feran orin kikọ Chete..
wikipedia
yo
O keko nimo nipa ere-onise ninu ede geesi (English) ni Yunifasiti Ibadan Ibadan..
wikipedia
yo
O tu keoo nipa ere ori-itage ni met fi school ni Ilu Lọndọnu,.aladese ti kọ itan fun Edge of Paradise ati Tinsel..
wikipedia
yo
She was the head writer for the series Hotel Majestic..
wikipedia
yo
Àjọ [YNaija]] kaa mọ́ àwọn ọmọ ogójì ọdún tí wọ́n ń kópa ribiribi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2018, ipa ti aladese ko ninu ere The lost cafe''' Gẹgẹ bi Kenneth Gyang ni won fi yan an fun Africa Movie Academy Awards gẹ́gẹ́ bí òṣèré tó peregedé jùlọ .Aláṣẹ ma ń kó eré àtìgbàdégbà fún MTV Shuga, nígbà tí wọ́n pe àwọn ọlọkàn-o-jọkan eré ṣúgà ní Shuga Down South..
wikipedia
yo
ó kọ́ ìsọ̀rí méjì fún iṣẹ́ náà sáájú kí wọ́n tó yàn án gẹ́gẹ́ bí olóòtú àgbà fún iṣẹ́ àkànṣe náà..
wikipedia
yo
Ní àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19, wọ́n ní kí ó kọ́ ìsọ̀rí eré ọlọ́jọ́jùmọ̀ fún MTV Shuga Alone Together kí ó sì sọ ipa àti ìdààmú tí arun korona ń mú bá àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
Wọ́n fi eré náà hàn ní ogúnjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2020.Wọ́n ṣe ère náà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, South Africa àti Côte d’Ivoire..
wikipedia
yo
Awon fiimu re MTV Staying alive Confusion na wa Hotel Majestic (TV series) (as head writer) lost cafe’’àwọn ami-eye ti o ti gba 2013 Best Supporting Actress - Nigeria Entertainment Awards 2015 Best Supporting Actress - Africa Magic Viewers choice awards 2018 Africa Movie Academy Award for Best Actress in a leading Roleàwọn itọkasiàwọn Ìtàkùn ìjásóde awon Eniyan AlààyèYear of Birth Missing (Living People)21st-21st Nigerian Actresses-21st Nigerian Writers-21st Nigerian Women Writers Writers, Screen ScreenWriters Film Actresses, Television Writers Television Writers Writers-Century screen..
wikipedia
yo
Neveen Dominic je osere, agbere jade, onisowoati oninurere ti o wa lati guusu Sudan ti on gbe ni ilu Kánádà.igbesi aye ara eni ilu South Sudan ni wwon bi Dominic si..
wikipedia
yo
Oni oselu ni baba e iya e si je osere.Ni igba ti o wa ni omo odun medogun ohun ati awon molebi re ko lo si ilu Calgari, Kanada nigba ti ogun waye ni ilu Sudan..
wikipedia
yo
Ni osu kakanla odun 2019, ohun ati oko re, ọmọ ilu Naijiria kan ti on gbe ni ilu Kanada, bi omo akoko wan.ise ise Idanilaraya Dominic je osere omo South Sudan akoko ti o ko ipa ninu fiimu ilu Naijiria Nollywood..
wikipedia
yo
O hún lọ ṣe igbejade fiimu jara Nollywood ti amo si "It's a Crazy World" o kó ipa ninu eré na..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹ́ta ọdún 2019, Eagle Online sọ wípé on gbèrò lati padà sí ẹnu jara ná ní ìlú Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Lẹhin ti o pada wa, o gba awọn oṣere Nollywood nlanla se ere, awọn oṣere bi Bob-Manuel Udokwu, Amanda Ebeye, Grace Amah, Moyo Lawal, Francis Odega, TunTun Aiyehin, ati Tochi Ejike Agbugbu ninu jara titi Nollywood.Òhun lo se eto atí olorin ni ose asa ati Oge titi New York ni ọdun 2018, fun Glenroy Marchi ohun ni oluda sile sileeen Dominic Cosmetics, ti o wa ni ilu Calgary, Alberta, Kánádà ti Ile Iise ero won wa ni United States ati Jemani..
wikipedia
yo