cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Lehin na won lo si ile eko African Film and Drama Academy (AFDA), ile eko nipa fiimu..
wikipedia
yo
Lehin wa igba na won pari eko nipa oludari ni Los Angeles campusi titi New York Film Academy.ise ise Ziqubu bere ere sise ni odun 2011 ni pase fiimu Man on Ground, eleyi ti o je ki ise ise re sun si waju..
wikipedia
yo
Wọ́n ti kó ère fun awon fiimu South African Television Soap opera gege bi Isidingo, Rhythm City ati fun Is'Thunzi ..
wikipedia
yo
wọn kò pa nínú kíkọ́, Gbígbéjáde àti dídarí supernatural eré dírámà ẹlẹ́yà mẹ́rin tí a mosi mọ́mọ́.Ní ọdún 2019, wọ́n shey oludari eré ẹlẹ́sẹ̀sẹ̀ MTV Shuga Down South.Àṣàyàn eréàwọn ìtọ́kasíàwọn líǹkì títà àwọn ènìyàn aláàyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1985..
wikipedia
yo
Bimbo Oshin je oni fiimu ti orile-ede Naijiria .igbesi aye ibẹrẹ ati ise a bi ni osu kerin ojo 24, odun 1971 ni Ipinle Ondo, ilu kan ni guusu iwo-oorun Naijiria ..
wikipedia
yo
Ó lọ sí yunifásítì ti Èkó ní bítí ó ti gba oyè Bachelor of Arts (BA) ní philosophy ..
wikipedia
yo
Bimbo bẹrẹ iṣẹ osere rẹ ni odun 1996 sugbon dide si idanimo lẹhin ti o se ere fiimu ti Yoruba ti odun 2012 ti akole re n je omo Elemosho.Fil ti a yan omo Elemosho kakanfo (2020) awon omo ilu tuntun (2020)ebun ati awon idanimo ni odun 2016, won bu ọla fun pelu aami ẹka ebun ni 2016 Afro-Heritage Broadcasting and entertainment and Awards.Awon itọkasi awon Ọjọ́ìbí ni 1971awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Ilgash Hadera (ti a bi ni ojo kini osu kankanla odun 1985) je osere Ethiopian-American ..
wikipedia
yo
O kò pa nínú fíìmù Baywatch ti Oj jáde ní ọdún 2017 gẹ́gẹ́ bi Stephanie Holden ..
wikipedia
yo
Ni ojo kankandilogbon osu kesan, Hadera bera si ni kopa Mayme Johnson, iyawo BuIMP Johnsonni ifi lole jara titi American , Godfather of Harlem lori Epix.igbesi aye ibẹrẹ a bi Hadera ni ojo kini osu kankanla ni ilu Harlem..
wikipedia
yo
Bàbà e AsfF je asasala Ethiopia tigrayan ati oludasili African Services Committee, NGO ti o wa ni ilu Harlem eyi ti o man shey iranlọwọ fun awọn oni irin ajo to wa lati Africa..
wikipedia
yo
Iya re Kim Nichols jẹ oludari Asc, ohun ati Hadera man yọ̀ǹda arowan le pẹlu oriṣiriṣi eniyan ki oto bẹrẹ iṣẹ osere ..
wikipedia
yo
Hadera ṣe iṣẹ olóúnjẹ fun ọdun mẹwa ki oto bẹrẹ ere ṣiṣe.O lọ si The Harlem School of the arts, atẹle nipasẹ Fijinlo H..
wikipedia
yo
Hadera lọ siwaju lati gba MFA ni Awọn ẹkọ Oro ati Iṣe lati RADA/King's College London.Iṣẹ ni ọdun 2010 Hadera jade ninu fiimu 1/20..
wikipedia
yo
Fun igba akokoohun ati Spike Lee ma Jon sise ni opolopo igba, oti kopa ninu Da Brick, The Blacklist, Oldboy, Show Me a Hero, Chi-Ra, Chicago Fire, The Punisnis ati she's Gotta Have It.Hadera se alabaṣiṣẹpọ gege bi Stephanie Holden ninu fiimu ọdun 2017 Baywatch, ati ni odun 2018 o se irawọ bi Kay Daniels ninu jara TV Billions..
wikipedia
yo
O ni o ni a ti nwaye ipa ninu awọn Showtime series Billions , gebi Akowe fun Billionaire Bobby Axelrod, dun nipa Damian Lewis .Filfitẹlifisiọnuàwọn itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1985àwọn Eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Ruth Negga ( ; ti a bi ni ojo keje osu kini odun 1982) je osere Ethiopian-Irish ti a mo fun ipa re ni jara telifisonu AMC Preacher ati ninu fiimu Loving..
wikipedia
yo
.Negga ti kopa ninu awon fiimu bi Capital Letters (2004) (ti a mo si Trafficked ni awon orilede mi), Isolation (2005), Breakfast on Pluto (2005) ati Warcraft (2016)..
wikipedia
yo
Awon ise imi tótí ko pa ninu re je BBC mini-series Criminal Justice, RTÉ Love/Hate, E4 Misfits, and ABC's Mar's Agents of S.H.I.E.L.D..
wikipedia
yo
Negga bere ipa re gegebi Tulip O’hare ninu Preacher ni odun 2016.Fun ipa re gegebi Mildred Loving ni Loving, won fi oruko Negga sile fun osere ti odaro julo ni Academy Award, Golden Globe Award , Independent Spirit Award , Critics’ choice movie Award osi gba ami eye Irish Film and Television Award fun osere ti o dara julo win tun fi oruko sile fun BAFTA Award gegebi osere tuntun ti odara julo..
wikipedia
yo
Ni odun 2020, won fun ni ipo kewa lori The Irish Times ninu awon osere Ireland ti o dara julo.igbesi aye ibere ati eko ni odun 1982 ni abi Negga si ilu Addis Ababa, Ethiopia, Iya re Nora je omo Ireland, Baba re, Dr Negga je omo Ethiopia..
wikipedia
yo
Awon obi re pade nigba ti Mama re n sise gegebi olókosi ni ilu Ethiopia..
wikipedia
yo
Negga ti o je omo kan ti awon obi re bi gbe ni Ethiopia titi to fi pe omo odun merin..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ kú nípasẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀, nígbà tí owa ní ọmọ ọdún meje..
wikipedia
yo
Ìlú Limerick, Ireland, ni odagba sí, òṣì tín gbé ní ìlú London láti ọdún 2006.Negga keko ni Samuel Beckett Centre ni Trinity College, Dublin, o gba oye ba ni eko imo sise ere.Iṣẹ Negga se ijade pelu fiimu Irish kan ti on je Capital Letters (2004), ipa Taiwo lo ko ninu ere na..
wikipedia
yo
Lehin igba na o ko pa Mary ninu Isolation ni odun to tele..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn ìgbà tí Neil Jordan rí Negga se ere, o ni lati tun ere na ko, owa pe akole re ni Breakfast on Pluto ki o ba le wa ninu ere na..
wikipedia
yo
Ọtí kópa ninu Colour Me Kubrick (2005), pẹlu John Malkovich, ati àwọn eré kúkú The Four Horsemen, 3-Minute 4-play ati Stars.Lórí telifisionu Negga ti kopa ninu awon ere Doctors, Criminal Justice àti jara Irish Love is the Drug..
wikipedia
yo
O kò pa Doris "Sid" Siddiqi ninu jara BBC Three èyí tí oje Personal Affairs, Lood Laura Aikman, Annabel Scholey àti Maquith McCoy..
wikipedia
yo
Negga kopa Rosie ninu awon jara alakoko titi RTÉ's Love/Hate.Negga kopa gegebi Dame Shirley Bassey ninu ere TV BBC Shirley ni odun 2011 osi gba ami eye IFTA osere ti odara julo fun ipa..
wikipedia
yo
Ipa re ninu Theartre je Duck ni Titus Andronicus ati Lay Me Down softly..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2007, obere ise pelu Irish theatrical Group ni Pan Pan Theatre..
wikipedia
yo
Ni odun 2010, o ko pa Ophelia ninu ifilole Hamlet lori itage..
wikipedia
yo
Otun fi ohun re kale fun ere Dark Souls II, okopa Shanalíkì, ti atu mosi "Emerald Herald".odun 2013 ni a gba Negga ki o wa kopa Raina ni jara American Agents of S.H.I.E.D.D.
wikipedia
yo
Ọsẹ afihan ninu ipele metadilogun titi eto na o ko ipa ninu fiimu Steve McQueeneyi ti ogba emi eye Oscar ti akole re je 12 Years a slave, sugbon won yo ipa re ninu ere na..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹdọgbọn oṣù kẹta ọdún 2015, Negga ko ipa Tulip O'hare ninu jara AMC, Preacher, ti o jade ni odun 2016.Ni odun 2016, Negga kopa ninu Loving, ti won se ifi lo le eh ni 2016 Cannes Film Festival lehin na ni Toronto International Film Festival..
wikipedia
yo
Fíìmù na dá lọ rí àwọn Lovings, toko tìyàwó ti wọn ni àwọ̀ ara to yato awọn ọdun 1950s ati 1960s ni Virginia, igbe yawo won fju ba ile ejo to ga ju lọ, ti esi won deni Loving v..
wikipedia
yo
Negga di ilu moka fun ipa yi, ati pe ogba yiyan ati emi yi lopolopo fun Ami eye Academy fun osere ti odara julo, Ami eye Golden Globe fun ese ori irin eyi ti o dara julo, ati BAFTA Rising Star Award.Negga kopa ninu ise Gate Theatre’ ti odun 2018 (Yaël Farber lo dari e) ti Hamlet, ti otun túnṣe ni St..
wikipedia
yo
Ann's Warehouse ni orisun 2020.Ìgbésí ayé ara ẹní Negga ati Dominic Cooper n fera wan ni ibere odun 2010..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ pàdé ní ọdún 2009 lórí eré orí ìtàgé phedre pẹ̀lú Helen Mirren..
wikipedia
yo
Awon mejeji jo n gbe ni Primrose Hill titi ilu London..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹ́ ra wan fún ọdún mẹ́fà; ṣùgbọ́n Negga ogba odun die ki awon oniroyin to gbo pe won o fera mo titi di osu kerin odun 2018..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn fún ìràwọ̀ tí ọ́n gòkè jùlọ ní ọdún 2006 ní Berlin Film Festival..
wikipedia
yo
Ọtí gba ìyìn rere fún ipa rẹ̀ gegebi Mildred Loving ninu fiimu odun 2016 eyi a pe ni Loving, oti gba Academy Award, Critic's choice, ati golden Globe Award nominations fun osere ti o dara juloawon itọkasi awon Ọjọ́ìbí ni 1982awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Àyọ FM jẹ ibudo redio ti aladani ni Akrá,olu-ilu Ghana..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ ibudo naa jẹ ohun-ini ati ṣiṣe nipasẹ Ile-iṣẹ ẹgbẹ ẹgbẹ media Multimedia Group Limited .O ṣee ṣe ariyanjiyan ibudo redio ti o jẹ olori ni Ghana ti o ṣe igbasilẹ ni ede Gẹẹsi.Awon eniyan olokiki Kookel Dumor Dzifa Bamfífọ́ Kojo Yankson Lexis Bill Manase Azure Nathaniel Attoh Malik dáàbu Daniel Dadzie Evans Leo Doreen Andoh Sammy-B Nathan Kwabena Apadesi Tommy Annan Apd Kwaku Eleori-do Kojo Trampong Ndaramah e apawu Gary Al-Smith..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, a yàn fún òṣèré tí ó dára jùlọ nínu eré Anilerin-in / TV jájá ní ọ̀dọ̀ àwọn àṣàyàn Áfíríkà fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù Backup Wife (2017)..
wikipedia
yo
ó tún nṣe ìràwọ̀ ROÁ TV, ìkànnì 329.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ a bí Ademoye ní ọjọ́ kẹrin, oṣù kẹrin , ọdún 1991, ní Lagos, gúúsù ìwọ̀ òrùn Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
ó gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga rẹ̀ láti ilé-ìwé Mayflower àti pé ó jẹ́ alumna ti ilé-ìwé Covenant níbití ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìṣàkóso ìṣòwò ..
wikipedia
yo
Ninu ìfọ̀rọ̀wáninilẹ́nu pẹlu iwe iroyin The Punch, o sọ pe Baba nikan ni o ṣe atilẹyin fun iṣẹ ti o yanlaayo .Iṣẹ ninu ifọrọwanilẹnuwo pẹlu iwe iroyin Daily Independent, o sọ pe iṣẹ oṣere rẹ bẹrẹ ni ọdun 2014 nigbati wọn gbe sinu fiimu kukuru Where Talent Lies Fiimu naa gba awọn iyìn lati Ayẹyẹ Fiimu Kariaye Afirika ..
wikipedia
yo
ó ṣe àpèjúwe Uduak Isong gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ rẹ̀, ẹni tí ó ṣe ìrànlọ́wọ́ fún láti wo ibi iṣẹ́ náà ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, a gbé jáde ní fíìmù ẹ̀yà àkọ́kọ́ It's about your husband èyítí ó tún ṣe nípasẹ̀ Isong..
wikipedia
yo
nínú àkójọ pọ̀ 2018 nípasẹ̀ ìwé ìròyìn Premium Times, Ademoye jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òṣèré márùn-ún tí ó ní àsọtẹ́lẹ̀ láti ní iṣẹ́ àṣeyọrí ṣaaju òpin ọdun ..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹrin ọdún 2018, ó ṣe alábáṣiṣẹ́pọ̀ pẹ̀lú Stella Damasus nínú Gone, tí Daniel Ademinọkàn ṣe oludari ..
wikipedia
yo
ó ṣe àpèjúwe ṣíṣe iṣẹ́ pẹ̀lú Damasus gẹ́gẹ́bí àkokò ìwúrí fún iṣẹ́ rẹ ..
wikipedia
yo
ní 2018 City People Movie Awards ,ó yàn fún ìfihàn ti ọdún, òṣèré tuntun tuntun tó dára jù lọ àti òṣèré Asese tó dára jùlọ..
wikipedia
yo
ipá rẹ̀ nínú Backup Wife tún jẹ́ kí ó gba yiyan fún Best Lead Role ní 2018' Nigeria Entertainment Awards..
wikipedia
yo
O gba awon ebun meji ni 2018 Best of Nollywood Awards fun ipa re ninu' Personal Assistant, o si gba ebun fun osere ti o dara julo ninu ipa atileyin Ossi gba yiyan fun Best Kiss in a Movie.Awon aṣayan ere rẹ awon ọ̀rẹ́bìnrin (2019) idile (2019) Kamsi (2018) gbigba rẹ (2018) Ìmọ́lẹ̀ ninu òkunkun (2018) oluranlowo ti ara ẹni (2018) Awon omo ilebinrin ti o nireti ti pari (2018) awon ojo hin tẹ̀hìn iyawo Spayinti iwe ito ito isele ti obirin ti obirin ara ilu ọ je nipa oko re se se Charmed meta ro iwo iwo eleyi je o (2016) nwa fun Baami) lero (2019) lero bi ọrun (2019) arọ (2019) apo pataki (2019) Olúfẹ̀ affy (2020) arọ (2020)Awon ami eye ni 1991 ni Ọjọ́ìbí Alààyè Tuntun..
wikipedia
yo
House of Gold(tí a gbé kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Family Runs lórí DVD) eré àwàdà ti Ghana àti Nàìjíríà ti Olùgbékalẹ̀ rẹ̀ jẹ́ Yvonne Nelson àti oludari rẹ̀ jẹ́ Pascal Amanfo..
wikipedia
yo
Àwọn ìràwọ̀ bíi Majid Michel, Yvonne Nelson, Omawumi Megbélé, Mercy Chinwo, Ice Prince Zamani Eddie Watson àti Francis Odega Kò pá nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
fíìmù náà n ṣàlàyé ìtàn àkọọ́lẹ̀ olóokòwò àti alajọṣepọ kan, dan Ansah Williams tí ó kú nípa àrùn àti pé wón sọ fún pé ó ní ọ̀sẹ̀ mẹfà láti gbé ayé..
wikipedia
yo
Ó ṣe ìpinnu pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ti agbẹjọ́rò rẹ̀ láti pe gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ padà sí ilẹ̀..
wikipedia
yo
Púpọ̀ jùlọ nínú wọn ni a bí láìsí ìgbéyàwó àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ tó jẹ́ èso ìbáṣepọ̀ ohunkóhunfin..
wikipedia
yo
Àtúnse isokan fa opolopo awon iyanilẹnu bi omo kookan se pada pelu eto ẹtan kan, eyi ti o ma ni awon abajade to pa ni Leerin.won se igbekale re ni 12, osu kerin odun 2013 ni Ghana ati ni 19 keje 2013 ni Naijiria ..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé fíìmù náà pàdé pẹ̀lú àwọnàtúnyẹ̀wò ìtara Odi ni gbogbogbo, ó gba àwọn ifiorukosile ní 2013 Golden Icons Academy Movie Awards, 2013 Ghana Movie Awards, 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards àti 2013 Zulu African Film Academy Awards ..
wikipedia
yo
fíìmù náà ṣe àfihàn ní Ghana ní ọjọ́ 12 Oṣu Kẹrin 2013 ati ni Nigeria ni ọjọ 19 ṣùṣùeje 2013, saájú kí òótọ́ ni ìgbékalẹ̀ èrè gbogbogbo ni nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba igbekale lori DVD pelu akole FamilyRuns ni osu Kọkànlá odun 2013 nipasẹ Henrikeasim Multimedia Concept.Wo eyi naa atokọ awọn fiimu Naijiria ti ọdun 2013awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Carl Reiner (March 20, 1922 – June 29, 2020) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ọtí kópa nínú oríṣiríṣi eré òṣì ti gba àmì ẹ̀yẹ púpọ̀.Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí Abdel Razek si Kafr Saqr, Sharqia Governorate ní ọdún 1970..
wikipedia
yo
O ti gbe ni ilu Yemen fun odun mefa.Iṣẹ o bere ise re gegebi modeli fun ipolowo oja..
wikipedia
yo
Iṣẹ osere ti o kọkọ se je jarar TV The thief I Love eyi ti o jade ni ọdun 1997..
wikipedia
yo
Awon ise re ti o ni okiki julo ni Hajj Metwali's family ni odun 2001, Mahmood pàṣẹri ni odun 2003, Sons of the Night ni odun 2007, Albaàní ni odun 2009, Zahra and her Five Husband ni odun 2010, Samara ni odun 2011, with Premeditation ni odun 2012, Life story ni odun 2013, The first Lady ni odun 2014, The Night ni odun 2015, Alláàyò ni odun 2016, land Air ni odun 2017 ati Against Unknown ni odun 2018 oti kopa ninu ere pupo; àwwọnted ere re ti oni okiki ju ni Gago Abdel Nasser ni 1999, About Love and Longing ni odun 2006, 90 minutes ni odun 2006, Zdu Níwọ̀n ni odun 2006, 45 Days ni odun 2007, Ona Hen Ni odun 2007, Master Omar Chinua ni odun 2008, ADCO ni odun 2009, Fa-Sori's Secret Regbé Ni odun 2009, Honor Crisis ni odun 2009, she's shop ni odun 2009, bon Saru ni odun 2010, Talk Me, Thank You You ni odun 2010, Redu ni odun 2012, Garc Ni odun 2013, Those Who are A are dead ni odun 2016 ati Karmòọ War war ni odun 2017.O gba ami eye fun osere ti o dara julo ni Alexandria International Film Festival fun ipa re ninu Ọba HenÀṣẹ..
wikipedia
yo
O tun gba ami ẹyẹ ti Mure d'Or fun osere birin ti o dara julo ni ilu Egypt ni odun 2013..
wikipedia
yo
O gba ami eye titi Dear Guest lati iwe iroyin Dear Guest gẹgẹbi oṣere ti odara julo ni odun 2018..
wikipedia
yo
O se adajọ fun idije Arab Casting pẹlu Kosai Khauli ati Carmen LebBO.igbesi aye ara eni Ghada Abdel Razek se igbeyawo ju ẹ̀kán lọ..
wikipedia
yo
Igbeyawio akoko re je si onisowo Saudi kan,Adel Gazzaz eyi waye nigba to je omo odun metadilogun; won ko ra won le ni odun 1994..
wikipedia
yo
Igbeyawo ekeji re je si onisowo kan ti o wa lati Port won ko ra le nitori iyatọ larin ojo ori won..Igbeyawo eleketa je si Helmy Sarhan ni odun 2001; won kora sile leyin odun kan..
wikipedia
yo
Igbeyawo ẹlẹ́kẹrin jẹ́ sí Walid Al Tábàèyí; Wọ́n kọra sílẹ̀ ní ọdún 2009..
wikipedia
yo
Igbeyawo ele karun je si Mohamed fódà Oniroyin kan ni odun 2011; won ko ra won le ni odun 2015..
wikipedia
yo
Obi ọmọ obinrin kan, Rotana Gazzaz, fun ọkọ rẹ̀ akoko osi ni omo omo meji..
wikipedia
yo
atún mọ́ Ghada Abdel Razek gẹgẹbi awọn irawọ ti o sun mọ́ President Ilu Egypt Abdel Fattah el-Sisi..
wikipedia
yo
Ni ojo keje osu karun odun 2020, Abdel Razek se igbejade pe ohun ti fe oludari Haiitham Zenita.Awon iseere Oniise rediofisaÌta tẹlifisiọnuawon itọkasiitọkasi tita tita Ghada Abdel Razek in imdbáwọn eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1970..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ wa lati ilu Cairo, iya rẹ si wa lati Sharqia..
wikipedia
yo
Asmaa ti feran ki o ma se ere lati igba omode re sugbon ko ri ere se nitori pe ko si ere itage sise ni ile-eko ti o lo, sugbon lehin ti o de ile-eko giga o ri egbe Tiata, o si darapo mo won nipasẹ egbe Tiata Atelier.Ni igba ti o darapo mo"Tiata Atelier" o ko ise lowo oludari Shadi Daly o si se orisirisi idije, eyi ti o se ni gbeyin ni "Magic Mix of Happiness" ti o dije ninu Arab Theater Festival fun ami eye "Sheikh Sultan Al Qasimi" fun egbe ere itage Arab ni odun 2016.Ere itage ti o koko se ni eyi ti o se ni ile-eko giga, ni abe akori “Life is Beautiful in Fine Arts", lehin igba naa, o kopa ninu ere ori itage ti akori re je "Ọnding Stable" ti ba Uadad se oludari re.Ni odun 2014, o kopa ninu jara lati 2010 Loved" eyi ti Maryam Al Ahmadi ni ipa kekere ni o ko nibe.A yan kale nipasẹ oludasiṣẹ Ahmed MedH Sade, ti o je oludari Tamer Mohsen, lati se ipa ti "Toka" ati lẹhin ti o ja gere ni awon idanwo, eyiti o yori si ipa ti o gba..
wikipedia
yo
Ẹ̀rù máa ń bàá láti dúró sí iwájú kámẹ́rà, nítorí kò ní ìgboyà láti kó ipa rẹ ninu eré náà..
wikipedia
yo
O feran ipa Taqa ti o ko, nitori ipa naa je titi aláàánú, sugbon o ni agbara.Abul se oludari "Melodrama" ni odun 2013, o tun kopa ninu "Hábhan", o tun se oludari Shadi Daly ninu ere "Dream plastic ti o kopa ninu..
wikipedia
yo
O tun se "Made in China" ati The Revolution of the Dead.Awon ise re ati awon fiimu rẹàwọn ami eye osere ti o dara julo ni "Eli Short Film Festival " ni odun 2019.Awon itọka síàwọn ona asopọ ita awon eniyan Alààyè Alààyè with unreviewed translations..
wikipedia
yo
Tamara èteìmọ̀ (bíi ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje, ọdún 1987) tí orúkọ ìnági rẹ̀ jẹ́ Tamara Jones jẹ́ òṣèré àti olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gbe ipo keji laarin awon osere binrin ni Nollywood ni odun 2013..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Port Harcourt níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ eré orí ìtàgé.Àṣàyàn àwọn eré àkòko Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Louis Barnes (Bii ní ojo kerindinlogbon osu kerin, odun 1974) je osere ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
O di gbajumọ fun ipa ti o ko ninu ere surviving Evil ni ọdun 2009..
wikipedia
yo
O ko ipa Miranda Barlow ninu ere Black SaEpo ni ọdun 2014.Ayé ati ẹkọ rẹ won bi Barnes si Ilu KwasZulu-Natal, o si gboye ninu imo Dramatic art lati ile eko giga ti University of Witwatersrand.Iṣẹ Barnes ti kopa ninu oríṣìíríṣìí ere bii Etyl, 7de Laan, Binneratically, scandal!, Sorted, ṣuburban Bliss ati S.O.àṣàyàn.Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ Fiimutẹlẹnunu]àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Mary KuKSIe Twala (Bii ni ojo kerinla osu Kesan-an odun 1939) je osere ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, Wwan yàn kalẹ̀ fún ẹ̀bùn Best Actress in a Supporting Role láti ọ̀dọ Africa Movie Academy Award . Twala ti kópa nínu oríṣìíríṣìí eré ìbílẹ̀ ní South Áfríkà..
wikipedia
yo
Comatose Vaya Beyond the River.Ikú Mary Twala kú ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje, ọdún 2020 ní àgọ́ mọ́kànlá ní ilé ìwòsàn àdáni ti ParkLane Private Hospital ní ìlú Johannesburg..
wikipedia
yo
Wọ́n sìn ní ọjọ́ kẹsan-an oṣù keje, ọdún 2020 ní ìlú Sòwẹ́tò.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sithembílẹ̀ xọlá Pearl Thuân (Bii ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù karun-un, ọdún 1989) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní South Afrika..
wikipedia
yo
Thusì ni okiki fun ipa Patricia kokung ti o ko ni èrè The no..
wikipedia
yo
O ko ipa Dáyánà Mampàsí ninu eré quantico ati Samkelo ninu eré Ife Catching feelings.Iṣẹ Thuân ṣe atọ́kùn fun eto Lip Synge Battle Africa lori MTV ati etv, o si ṣe atọ́kùn fun eto ộrộ ti wọ́n pe akole re ni moments lori EbonyLife TV..
wikipedia
yo