cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó kópa nínu eré Ìsìndindin gẹ́gẹ́ bíi palẹ̀sa Motal..
wikipedia
yo
Òun pẹ̀lú DJ Warras àti Luthando Shosha jọ ṣe atọ́kùn fún ètò Live AMP..
wikipedia
yo
Ó farahan nínú orin Pearl Thuts, èyí tí Emtẹ̀ẹ́ kò.Àṣàyàn àwọn eré Refiimutẹ̀léfíìsìnu] Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mary dátà Uránta jẹ́ òṣèré àti olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bíi sí ìlú PortHarcourt, ibẹ̀ sì ni ó gbé dàgbà..
wikipedia
yo
O wa lara awon to dije fun ipo obinrin ti o rewa julọ ni ile Niger Delta, o si gbe ipo keji.Upadeta bẹrẹ ere sise ni odun 2000 pelu ere girls hostel..
wikipedia
yo
Ni ọdún 2006, ó di gbajúmọ̀ fún ipa ti ó kó ninú ere Secret Mission..
wikipedia
yo
Ó dá ẹgbẹ́ Mary Uranta Foundation kalẹ̀ láti pèsè ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọde ní ìlú Atìbo..
wikipedia
yo
O ti gba ẹbun lati ọdọ City People Awards ati African Youth Ambassador Award.ibẹrẹ Pẹpẹ ayé ati Eko rẹ Uranta dagba ni Ilu PortHarcourt ni Ipinle Rivers..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Holy Rosary Girls Secondary School kí ó tó tẹ̀síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Rivers State University of Science and Technology níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ DetoMispata Administration.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Diza Aliyu (Bii ni ojo kìíní osu kefa odun 1989) je osere ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
O jẹ aṣoju fun ile ise MTN Nigeria ati Indomie noodles..
wikipedia
yo
O gba ẹbun Oṣere to dara jù lọ ni ọdun 2013 lati ọdọ Nollywood Awards, o si gba ẹbun lati ọdọ Kannywood ati MTN ni ọdun 2014.ibẹrẹ Pẹpẹ Aiye rẹ wọn bi si Ilu Libreville ni orile ede Republic of Gabon..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ Gàbọ̀n ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ adáwa ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Iṣẹ́ dìza dara pọ̀ mọ́ kannywood lẹ́yìn ìgbà tí ó padà sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ere ṣiṣe ni ọdun 2009 ninu ere Artàbúo darapọ mọ Nollywood ni ọdun 2017, o si kopa ninu ere Lagos Real FAke Life..
wikipedia
yo
Ni Oṣu kejila, ọdun 2018, Ile iṣẹ Nascon Allied PLC, fi ṣe aṣoju wọn..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ náà sì wá lati ṣàpese Káka ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́, ìrẹ àti ìlera tí ó péye fún àwọn aláìní.Aṣa àwọn eré ẹlẹ́mọ̀ ìtọ́..
wikipedia
yo
Estelle Lebost (June 5, 1914 – October 25, 2008) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Vyoqueque Shanda bẹ́yà Mputu jẹ́ òṣèré tí ó wà láti ìlú Congo..
wikipedia
yo
Ogba ami eye Africa Movie Academy Award fun osere iwaju ti o dara julo fun ipa re ninu Felicite .igbesi aye ibere a bi Mputu osi dagba si ilu Kinshasa, eyi ti o je olu ilu orile-ede olominira oselu ile nkoise ni odun 2017, o ko pa ninu Felicite ni a se agbeyewo e ni 67th Berlin International Film Festival..
wikipedia
yo
O ni ohun feran ipa na nitori pe ojuwe awon obinrin gege bi awon eniyan ti ole da duro, ti ko nilo iran lowo awon okunrino gba emi eye osere birin ti o da ra julo ni Africa Movie Academy Awards eleketala eleyi ti owaye ni Ilu Eko, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
atu fun fiimu na ni àyẹ̀wò gẹ́gẹ́bi Sègalẹ́sẹ̀ entry fún 90th Academy Awards, eleyi jẹ́ fíìmù àkọ́kọ́ ti ìlú Senegal tí a fi kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ na...
wikipedia
yo
The Times juwe ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́bí èyí tí yẹ kí ọgbà àmì ẹ̀yẹ nítorí òní ìgboyà.Ẹ ni ó lò fún àyẹ̀wò, olùdarí Alain Gomisoso fẹ́ fún ní ipá nínú eré ná.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyè..
wikipedia
yo
Khabónì qushowinterpret: Ni ojo keji Yoruba, odun 1981) jẹ oṣere, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, onijo ati olorin ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi òṣèré bìnrin tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Boston International Film Festival Awards, wọ́n sì yàán kalẹ̀ fún ẹ̀bùn òṣèré gébìnrin tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Florida Film Festival àti African Movie Academy Awards fún ipa Dora tó kó nínú eré Dora's Peace..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó kó ipa Segu ZamDela nínu eré Ìsìndì.Ó ṣe atọ́kùn fún ètò Fix My Love ti ilé iṣẹ́ bet gbé kalẹ̀, ó sì gbajúmọ̀ fún ipa Maxine tí ó kó nínu eré The Wild.Gẹ́gẹ́ bíi oníjó, ó ti ṣe atọ́kùn àti Adájọ́ fún oríṣiríṣi àwọn ètò ijó bíi Dance Your Butt Off, step Up or step Out.Iṣẹ́ Qubù di gbajúmọ̀ fún ipa Dìbo tí ó kó nínu eré Muvfọwọ́ ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
O ti kopa ninu awọn ere bii she is King ati Isidingo.Ni ọdun 2017, o gba ami eye gege bi oṣere binrin to dara ju lọ nibi ayẹyẹ Boston International Film Festival..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹwàá, Ọdún 2017, ó ṣe atọ́kùn fún ètò tí wọ́n ṣe fún àwọn olùó ní South Áfríkà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Dolly RTHE (bíi ní Ọjọ́ kejì, Oṣù kẹrin ọdún 1928) jẹ́ òṣèré àti olórin ní orílẹ̀ èdè South South Afrika..
wikipedia
yo
Ó kú ní ọjọ́ kẹrìndíndínlógún oṣù kẹsàn-án, ọdún 2004.Iṣẹ́ ní ọdún 1984, nígbà tí ó kọrin ní bí ti àwọn èèyàn ti ń ṣe fàájì ní ìlú Johannesburg, ni àwọn kan lọ bá wípé kí ó wá ṣiṣẹ́ lọ́dọ̀ wọn, kò pẹ́ díẹ̀ tí ó wà lọ́dọ̀ wọn ni ó di gbajúmọ̀ láàrin ìlú.Ẹ di gbajúmọ̀ ní ọdún 1949, nígbà tí ó lọ kọrin nínú eré Jim comes tó jó'burg.Nígbà tí ẹgbẹ́ olórin Alf Herbert’s African Jazz and variety Show bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1954, Ra-the darapọ̀ mọ́ wọn, ó sì ma ń bá wọn kọrin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, Rathebẹ̀ gba ẹ̀bùn Lifetime Achievement Award níbi ayẹyẹ South African Music Awards..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2004, ó gba àmì ẹ̀yẹ Order of LoKhaga fún ipa ribititi ó ti kó nínú orin kíkọ.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Jo-Anne Reyneke (bíi ní Ọjọ́ kejì Oṣù kẹfà ọdún 1988) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Afrika tí ó gbajúmọ̀ fún ipa Pearl tí ó kó nínú eré Muvhando àti prudence O' nínú Ryranti City.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀yí ayé rẹ̀ wọ́n bíi sí ìlú vereeniging ní ilé Guate..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Russell High School, níbẹ̀ sí ni ó ti nifẹ sí eré ṣíṣe..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ Movich Film and Television School ní Durban níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ orin kíkọ àti eré ṣíṣe.Iṣẹ́ Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ The Playhouse company, níbi tí ó ti kópa nínú eré The Game..
wikipedia
yo
Duma Nopalov tí ó jẹ́ olùdarí eré MuvMaro, fún Reyneke ní ànfààní láti kópa nínu eré náà gẹ́gẹ́ bíi Pearl, èyí sì ló jẹ́ kí Reyneke ti gbajúmọ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, ó fi eré Muvfọwọ́ sílẹ̀, ó sì kópa nínu eré Intersexions àti Rhythm City ní ọdún náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó kópa nínu eré Efe tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Black Tax.Igbeyawo rẹ̀ ní ọdún 2008, jo-Anne Reyneke se igbeyawo pelu Thami MngQ.
wikipedia
yo
Wọ́n bíi ọmọ meji tí orúkọ wọn jẹ́ UVolwe) ní ọdún 2013) ati Lunda ní ní ọdún 2015)..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2018, ohun ati ọkọ rẹ pinya.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Rachel Mwanza je osere ti o wa lati orile-ede olominira oselu ile nko , a mo ju lo fun ipa re komọ̀nà ninu fiimu War Witch (Rebelle) ti o jade ni odun 2012..
wikipedia
yo
Kí ó tó rí ipano kọ́, kò ni ilé, àdúgbò Kinshasa ni ó man sùn.Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1997 ni àbí Mwanza ní Mgbẹ́-Map, oje ọmọ ẹ̀kẹta nínú ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbí ẹ̀ bí,Kasaï Province ni oti ìlú igba ọmọdé e.bàbá rè fi ohun, ìyá rè àti wwon èyí tókù rè kalẹ́ kalẹ́, ó ní ohun awa báwọn ọgbà ló di, eleyi fa sábà bí ohun àti àwọn ọmọ ìyá ìyá ọ̀sẹ̀ lọ sí ilé ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó ya wòlĩ èké kan sọ fún ìyá Mwanza pé aje ní Mwanza..
wikipedia
yo
O gba owo ti o fi yo emi Èṣù kuro ninu ara Mwanza, sugbon ni igbeyin, won le sita.Mwanza lo opolopo odun ni adugbo, ki oto kopa ni nu ere ilu Canada War Witch (Rebelle)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013 ó kó ipa nínú eré Kinshasa Kids Eleyí tí Marc-Henri Wjn kọ tí òṣìtún darí.Ó padà lọ sí Montreal, ní ibi yí ni ọtí lọ sí ilé ẹ̀kọ́ École Lucien-Page ọdẹ tún bẹ̀rẹ̀ sí gbé pẹ̀lú ẹbí Anne-Marie géinas-s, olùdarí fíìmù War Witch.Iṣẹ́ eré ṣíṣe wọ́n fún ní ipa Rebelle lẹ́hìn ìgbà tí Olùadri eré Kim Nguyen, agbeiṣẹ́ síta Pierre Even àti Marie-Claude Polójúkojú rí nínú fíìmù oníròyìn nípa àwọn ọmọ àdúgbò Kinshasa..
wikipedia
yo
Nitori ko lọ ile eko ko le ko, ko si le ka, eleyi ni awon oni fiimu se se eto ati lo ile eko fun titi yo fi pe omo odun mejidinlogun..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2013, wọn fun ni iwe ìwọ̀lú, lati jẹ ki o wa si Academy Awards..
wikipedia
yo
O fi asiko yi na se ipolowo Rebelle ni ilu Amerika.Ipa Mwanza ninu Rebelle je ki o gba ami eye orisirisi gegebi Silver Bear Award fun osere ti o dara julo lati owo Berlin Film Festival, Tribeca Film Festival ati Vancouver Film Critics Circle ni odun 2012, otun gba ami eye osere ti o dara julo ni 1st Canadian Screen Awards ati Quebec Cinéma.Mwanza pada ko iwe ti o pe akole re ni survivre pour voir ce Jour, eleyi ni ofi so awon ohun ti oju e ri ni igba ti o wa ni omode, Nowe lero pe iwe na a fun awon odo ni Ireti ati pe ofe je ki awon eyyan mo ni pa awon omo Egba ti owa ni adugbo Kinshasa..Awon Ìtọ́kasí sii sii awon eniyan alààyẹ̀ awon Ọjọ́ìbí ni 1997..
wikipedia
yo
Shaen Surtie-Richards (Bii ni ojo keje, osu karun-un, odun 1955) je osere ni orile ede South Afrika..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùdarí ilé ẹ̀kọ́, ìyá rẹ̀ sì ju olùkọ́.sur-tiẹ̀-Richards jẹ́ olùkọ́ fún àwọn ọmọdé láti ọdún 1974 di ọdún 1984..
wikipedia
yo
O gba ami eye gege bii osere to dara ju lo lati odo fleur du cap Theatre Awards fun ipa jara ti o ko ninu ere Tẹ́ve en Kobai (Hello and Goodbye)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, ó gba ẹ̀bùn míràn láti Ọ̀dọ́ fleur du Cap Awards fún ipa tí ó kó nínú eré Shirley Valentine ní ọdún 2008..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó gba ẹ̀bùn elere tó gbajúmọ̀ láti ọ̀dọ Herrie Prize níbi ayẹyẹ Klein Karọ̀ọ́ Arts Festival..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán kalẹ̀ fún ẹ̀bùn òsèré tó tayọ jùlọ ní ọdún 2014.Ó gba ẹ̀bùn láti Odò nálẹ̀dí Theater Awards ní ọdún 2015.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ephex Kanana Gichuru (ti abi ni ojo kerinla osu kejila odun 1986)jẹ osere ati olugbalejo ori telifiosnu omo ilu Kenya..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bíi òṣèré pjẹ gbajúmọ̀ fún àwọn ipá rẹ̀ nínú àwọn jara tẹlifísíọ̀nù Noose of Gold, Demigods àtihow to Find a Husband..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi olugbalejo ori afẹ́fẹ́, oye ki ọgbẹ eto Interior Desist jade, ki oto se alaisi..
wikipedia
yo
O se igbeyawo pelu RIchard Wainaina.Iṣẹ Gichuru ti kopa ninu orisirisi igbe jade gege bi Noose of Gold ni odun 2010 ati Demigods ni odun 2011..
wikipedia
yo
Eyi to je titun ninu awon eto re ni How to Find a Husband ati eto Interior Designs.Iku ni gede ago mewa aro ni ojo kejilelogun osu Kesan odun 2015, Nana ririn ajo ninu oko BMw e ni opopona fori nigba ti ọkọ re lo kọlu oko nla..
wikipedia
yo
Oku ni ẹ̀ṣẹ̀kẹ́ṣẹ̀, òkú ni ọmọ odun mejidinlogbon.Iku e waye ni ojo mewa lẹhin igba ti o se asọtẹlẹ ikú e lori ero aye lujara..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe ètò ìrántí ẹ̀ ní ọjọ́ Jọdọgbọn oṣù kẹsan ọdún 2015 ni ilé ijọsin ijo Methodist titi rukaka..
wikipedia
yo
Wọ́n sin ní ọjọ́ kejì Oṣù Kẹ̀wá Ọdún 2015 ní ìlú Ẹ Kaaga ní Meru.Àwọn àṣàyàn eréàwọn Ìtọ́kasíàwọn ọ̀nà àkòpọ́pọ́ ìta àwọn àwọn Ọjọ́lọ́ ní 2015àwọn Ọjọ́ìbí ní 1986..
wikipedia
yo
Patricia Wangechi Kihoro (ti a bini ojo kerin osu kini odun 1986) je osere, olorin ati adari eto radio ti owa lati ilu Kenya..
wikipedia
yo
O di olokiki nitori pe o kopa ni ipele ẹkẹta titi Tusker Project Fameeleyi ti o de igbeyin idije na..
wikipedia
yo
Ni pa sise ere, akoko ere ti o kopa ninu re je ere Miss Nobody eleyi je ki o gba yiyan ninu ami eye Kalasha Awardsasiwaju osere ti odara julo ni odun 2012..
wikipedia
yo
Ninu jara TV o jẹ ọkan ninu oṣere ti o pataki julọ ninu Groove Theory fiimu olorin, osi kopa ninu Demigods, Changes, Rush ati Makutano Junction..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi oṣiṣẹ redio ọti sise pẹlu one FM ati HomeBoy FM.igbesi aye ibẹrẹ wọn bi Kihoro ni Oṣu Kini ọdun 1986, osi dagba si Nairobi, olosi ile iko Shepherd Junior Primary School fun Eko akobere, lehin na olosi Moi Girl's School, ni Nairobi..
wikipedia
yo
O lo si ile eko giga titi Moi Universitynibi ti oti keko Science ati psychology..
wikipedia
yo
Ni ile eko giga ni oti lo dije ni Tusker Project Fame.Iṣẹ 2009 si 2012 ni osu keta odun 2009, Kihoro ko pa ninu ayewo fun awon ti o ma kopa ninu Tusker Project Fame..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010 wọ́n lò nínú eré orin fún orin just a band ha-he tí ó dá lórí akọni Makmende..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011 ó kó ipa Pet Nanjala ní jara Changes.Ní ọdún 2011 kana otun kópa nínu eré Miss Nobody, eleyi ni ó jẹ́ kí won yàn fún àmì ẹ̀yẹ Kalasha ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, owa lára àwọn tí okopa nínu fíìmù orin tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Groove Theory..
wikipedia
yo
O ko ipa Biscuit, ololufe Zamm ninu ere ti oda lori igbesiaye awon omo ile eko Victoria University.odun 2013 si 2014 ni odun 2013 o ko pa ninu ereori telifisonu the FatÌyanu Uuriyi ni oje ki ohun ati awon dábùú se awokose asa ti awon eyan Efik ni apa guusu orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ni odun 2014 oko ipa Nana ninu jara Rush.O se ere pelu Janet Mbububu, Wendy Kimani, Wendy Sankale and Maryanne Nundo.odun 2015 titi di Jonathan ni odun 2015, o ko ipa omo Maqbul Mohammed ninu jara Makutano Junction..
wikipedia
yo
Ni odun 2018 Kihoro ko ipa Josephine, iyawo titun si ikan ninu awon akopa iwaju titi fiimu Rafikiaworan iwoyeaṣayan ereawon fiimu ati tẹlifisiọnuawọn itọkasiawọn ọna asopọ ita Patricia Kihoro at SoundCloud eniyan Alààyè E- Ọjọ́ìbí ni 1986 with Hcar..
wikipedia
yo
Nana Hill Kagga Macpherson ti atun mo si 'Nana Kagga-Hill tabi 'Nana Hill' je omo orile ede Uganda, oje osere, ako ere, onimo ero ati agbọrọsọ iwuri..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ ẹ̀ nínu The Life, Beneath the lies - The series Ggbi akọ eré àti agbe eré jáde pàtàkì àti gẹ́gẹ́ bi òṣèré nínú Star Trek., ọ̀kan nínú àwọn adájọ́ Miss Uganda ní ọdún 2018.A bí Kagga si ilu Nairobi, Kenya fún àwọn òbí tí ó wá láti Uganda, kan nínú àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ onímọ oníkàn ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
Kagga je Muganda, otun je Omoba birin ni awon eya BaGan..
wikipedia
yo
Kagga je omo eleketa ninu omo mefa ti awon obi e bi..
wikipedia
yo
Ni asiko ti won bi, awon obi e wa lehin odi, ni asiko oludari idi amin Kagga dagba si ebi ọlọ́lá..
wikipedia
yo
Yato fun baba ati baba-baba e, awọn ọmọ iya e mẹrin na jẹ onimo ero..
wikipedia
yo
O gbo ede Gẹẹsi ati ede Luganda.Eko Kagga pari ile eko alakobere ni Kampala Parents School..
wikipedia
yo
Ó darapọ̀ mọ́ Gäza High School, ilé ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ obìnrin fún O-Levels..
wikipedia
yo
O se A-Levels ni Red Maids School, Bristol, Ile ẹkọ awon omo Ibinrin ti o ti dagba ju ni UK..
wikipedia
yo
Kagga loai il eko giga University of Birmingham, Birmingham, UK, ni ibi yi ni oti ko eko imo ero nipasẹ titi epo robi..
wikipedia
yo
Ni asiko isimi o ma n lo si Uganda lati se adari eto Jam Agenda lori WBS.lehin ti o pari ile eko giga, Kagga ko lo ilu Florida ni ile USA, lehin igbana otun losi New Mexico ni Ilu Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O sise ni ile ise Laguna gegebi oni mo ero ni Laguna nigba ti won sise pelu awon ologun.Hollywood (gege bi Nana) Kagga gbero lati se ise osere ni ilu Los osi osi ni awon aseyori kankan..
wikipedia
yo
Nínú eré ìtàgé títí Amẹ́ríkà, Kagga kó ipa Mercy ninu ere Butterflies of Uganda ti Darren Dahms se, won yan eré na fun ami eye NAACP..
wikipedia
yo
Kagga ti kopa ninu opolopo fidio orin lati owo awon olorin bi P!nk, Amy Winehouse, sting, Lenny Kravitz..
wikipedia
yo
Kagga ti ko ipa ninu ipolowo orisirisi fun awon ilese KFC, Coors light, Pepsi, DSW, Microsoft, Apple, Tylenol, DODOS..
wikipedia
yo
Ni igba ti owa ni ilu Amerika, Kagga ni ile itaja fun awon nkan ti oti pe ti osi ni iyi ni Santa Monica ti o pe ni a Vintage Affair.Ni Uganda Kagga pada si ilu Uganda ni odun 2009, o da ile ise sile ti oje Savannah MOON Ltd..
wikipedia
yo
Savannah MOOD labe akoso, Savannah MOON Productions won se agbejade ere The Life ti won se afi han e ninu M-Net, jara telifisonu Beneath the lies - The series,lowolowo bayi won se afihan e lori Urban TV ati MTN Uganda, How We See It..
wikipedia
yo
Savannah MOON tun gbe ere kan ti won pe akole e ni The Last Breath pelu Kampala Film School..
wikipedia
yo
Savannah MOON sise orisirisi lowo, ikan ninu e ni Taking time, jara telifisonu ti on bo lona..
wikipedia
yo
Kagga da egbe kan si le You Are limitless (alyal) o da si le ki oba le je nkan ti oma mu ori awon omo Afrika wu, ki won ba le se gbogbo nkan ti won fe se laye..
wikipedia
yo
Kagga tun sise pelu ile epo robi nla kan ni ilu Uganda.àṣàyàn eregegebi osereeretelifisonuere Itagegegebi atukọ̀ egbeawon itọkasiawon ona asopo ita Nana Kagga Facebook Profileawon Ọjọ́ìbí ni 1979awon Eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Flavia Tumusiime Flavia je osere ati agbalejo ori redio ati tefisonu ti owa lati ilu Uganda,emcee ati on 30 Days of Flavia.O man se eto ni ọ̀gànjọ́ owuro lori ikani 91.3 Capital FM redio ni Kampala,o ti seto tele ri ni morning @ NTV lori NTV Uganda ọ̀yẹ̀ na ni o tin se eto gegebi jaja fun Channel O..
wikipedia
yo
O ko ipa Kamali Tenywa ninu jara ti Nana Kagga se, ti akori re je Beneath The Lies - The series lati odun 2014 titi di odun 2016 oti sise pelu eto Guinness football Challenge.Ìgbésí ayé ibẹrẹ ati eko won bi Tumusiime ni odun 1989 ni Kampala, o je omo kan soso ti Enoch Tumusiime ati Christine ásìimwe bi, won wa lati ilu Kabalẹ, ni guusu-iwo-oorun Uganda..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ Theresa kíbíbí, lehin wà igbano olosi Kitante Hill Secondary Schoolfún ó àti A Level ẹ..
wikipedia
yo
Olo si ile eko giga Makerere University Business School ni ibíyìí ni oti gba oye Eko ile iwe giga ninu owo ilu okeere.tẹlifisiọnu Tumusiime je agbalejo ori telifisonu lati igba ti o wa ni ewe..
wikipedia
yo