cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2019 ó kéde pé òhun ó má ta ọjà òhun ní ìlú Nàìjíríà àti Ghana .nínú ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tí ara ẹni tí àrírí ẹ̀ jẹ́ "Beauty From The Ashes of War" ó sọ ìtàn ayé e gẹ́gẹ́bí Alasasa tí ó wá láti South Sudan, ó sì sọpé ilé iṣẹ́ iṣẹ́ oge ohun jẹ́ fún ìgbìyànjú àwọn obìnrin.Iṣẹ́ inú rere ní àsìkò àrù COVID-19, ó ṣe àgbékalẹ̀ bí ọtí ma fún àwọn èyàn ẹ̀ ẹgbẹ̀rún ojú marun ní oúnjẹ..
wikipedia
yo
Maria Lasaru (ti a bi ni ojo karun un osu karun un odun 1989) je osere ati o nse fiimu omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni o gba ami ẹẹ lori fiimu awon eniyan ilu fun osere ti o ni ileri ti o dara julo ni ibi ebun ere idaraya ti i awon eniyan ilu (City People Entertainment Awards) ti odun 2018, won si tun yan an gege bi i osere ti o dara julo ninu ipa oludari ni odun kanna an nibi ayeye ebun fun awon osere Nollywood ti o dara julo (Best of Nollywood Awards).ibẹrẹ aye rẹ ati Eko Lasaru wa lati Ipinle Abia ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Ábíá wà ní agbègbè Gúúsù ìla òòrùn ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ́wọ́n tí ó jẹ́ wípé àwọn ẹ̀yà Ìgbò ni wọ́n wà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ukwa ti o wa ni Ijoba Ibile ila-oorun ni Ipinle Abia gangan ni Lasaru ti wa..
wikipedia
yo
Ìdílé ẹlẹ́ni mẹsan an ni a bí Lasaru sí èyí ti ìyá, baba pẹlu àwọn ẹ̀gbọ́n ati àbúrò rẹ̀ wà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìbejì nínú ẹbí yĩ àti wípé òun àti èkejì rẹ̀, Joseph tí ó jẹ́ ọkùnrin ni wọ́n bí gbẹ́yín..
wikipedia
yo
Nígbà tí Lásárù ti lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama tí ó sì ti gba ìwé ẹ̀rí moyege ní pàtàkì ti girama (West African Senior School Certificate), ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Ibadan (University of Ibadan) níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ gba ìwé ẹ̀rí tí ó munadoko lórí I Ala-ilẹ (Geography).iṣẹ́ rẹ̀ Lásárù tí ó jẹ́ olókìkí jùlọ nínú àwọn ipa tí ó ti kó nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ti Nollywood, ó ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí í alawose ní ọdún 2002 kí ó tó wá darí lọ sí ilé-iṣẹ́ fíìmù ti Nàìjíríà ní ọdún 2009 pẹ̀lú fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Waiting Years"
wikipedia
yo
Lasaru ri ipa kan ko ninu fiimu yi latipase iranlowo Gbenro Ajibade eni ti o ṣafihan re si John Njamah, eni ti i se oludari fiimu yi ti o si tun wa fun un ni ipa ti yio ko nigbeyin ninu fiimu ti a ti daruko re tele..
wikipedia
yo
Lasaru dari iṣafihan fiimu kan ti akọle rẹ n jẹ "Dance To My Beat", eyi ti o tun gbe jade ni ọdun 2017..
wikipedia
yo
Lasaru gege bi i alawose ti fi arahàn ninu orisirisi awon ikede ti ile-ise Airtel ati MTN ti se.awokose ninu ifọrọwanilẹnuwo pẹlu awon oniroyin ti iwe iroyin Vanguard, Lasaru daruko Omotola Jalade Ekeinde ati Joke Silva ti won je gbajugbaja osere Nollywood gege bi i awon ti oun n wo ko ise won ninu ise fiimu ni Naijiria..
wikipedia
yo
Ninu ifọrọwanilẹnuwo miran an pẹlu awọn oniroyin iwe iroyin The Punch, Lasaru daruko osere binrin ọmọ ile Amẹrika ti oruko re n je Kimberly Elise gege bi i okan lara awon ti oun feran nitori awon ise re ti o ti gbooro.ami eye ati yiyan Lasaru gba ami eye lori i fiimu ti awon eniyan ilu fun osere ti o ni ileri ti o dara julo eyi ti o waye ni City People Entertainment Award ti odun 2018..
wikipedia
yo
a yan Lasaru gege bi i osere ti o dara julo ni ipa ti oludari, eyi ti o waye nibi awon ebun eye ti BON ni odun 2018..
wikipedia
yo
Wọ́n yan Lasaru níbi ayẹyẹ ti 2020 Africa Magic Monvr's choice Award gẹ́gẹ́ bi í alátìlẹ́yìn osere tí ó dára jùlọ lórí oríṣiríṣi ipa kiko ninu un fíìmù tàbi telifisanu fún fíìmù ti "Siins 12".Ìgbésí ayé rẹ̀ Lásárù wá láti ìdílé ẹlẹ́ni mẹ́sàn án..
wikipedia
yo
Òun àti ìkejì rẹ̀ tí ó jẹ́ ọkùnrin ni wọ́n jẹ́ àbígbẹ̀yìn ìyá wọn..
wikipedia
yo
Pamela NobaVete (Bii ní ọdún 1963) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà.Wọ́n bí Pamela sí orílẹ̀ èdè Ethiópíà, ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè South Áfríkà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Royal Welsh College of Music and Drama ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, NodVete bẹrẹ ere ori Oriwe, o si di gbajumọ nipa ere Gene..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí òun àti ọkọ rẹ̀ pínyà, ìrònú dé bá, ó sì ní oríṣiríṣi ìsọ̀rọ̀, ó ní ìgbà kan tí ó ń gbé nínú oko rẹ̀, tí ó wá ń ta aṣọ rẹ̀ fún oúnjẹ àti sìgá.Ní ọdún 2004, ó kó ipa Thangdi nínú eré Zulu Love Letter.Ní ọdún 2012, ó kópa gẹ́gẹ́ bí Mandy kamara nínú eré Cọ̀rọ̀Nation Street..
wikipedia
yo
Halima Abubakar ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejila oṣù kẹfà ọdún 1985..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Afro Hollywood Best Actress Award.Ìgbé ayé rẹ̀wọ́n bí Abubakar ní ìpínlẹ̀ Kano , àmọ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ kogi ni..
wikipedia
yo
O si tun lọ si Ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Ipinle Kano..
wikipedia
yo
Ó tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ àkọ́kọ́ ní u ìmọ̀ sociology ní ilé-ẹ̀kọ́ báyéro University ní ìpínlẹ̀ Kano..
wikipedia
yo
Abubakar fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òun sì ní ìbálé ní oṣù kẹwàá ọdún 2018.Ní inú oṣù kẹrin ọdún 2020, ó kéde pé òun bímọ ọkùnriníṣẹ́ rẹ̀ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré tíátà ní ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré rejected..
wikipedia
yo
9un ló dá iṣẹ́ Modehouse Entertainment, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ igborin jáde.Àwọn Fíìmù resLip of Fatetears of a ChildSecret Shadowsgangster Paradiselara Mamamen in Loloctedcted Castleamípped Ivy Ivy of White huntersáwọn Ìtọ́kasíàwọn ànile ìjáIMDroko TV People from Kano state-21st Nigerian Actresses Of University Kano Aluhanàwọn ènìyàn ÀAlààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1985..
wikipedia
yo
Simone Pretorius (bíi ní Ọjọ́ Kejìdínlógún Oṣù Karun-un Ọdún 1990) jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa irma Hupel tí ó kó nínú eré Vir Die Vols..
wikipedia
yo
O tun gbajumọ fun ipa jọNY ti o kọ ninu ere Hotel, eyi si je ki o gba ami eye gege bi osere binrin to dara ju lọ lati odo South African Film and Television Award ni ọdun 2018..
wikipedia
yo
Eré tí ó fi kọ́kọ́ di gbajúmọ̀ ní 7de Laan(2013-2015) níbi tí ó ti kó ipa Nadia, èyí sì jẹ́ kó gba ẹ̀bùn òṣèré tuntun tó dára jù lọ ní ọdún 2014 láti ọ̀dọ Royalty sọWánà Awards.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kàrún-ún ọdún 1990 ní ìlú Pretoria ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà..
wikipedia
yo
Awon obi re je ajagun fun orile-ede South Afrika.O gboye ninu ere itage lati ile eko giga ti Stellenbosch University ni odun 2012.Iṣẹ leyin ti o pari ise pelu 7de Laan ni odun 2015, o lo si ile eko fun ere sise eyi ti Diane VeNora gbe kale fun ose meta ni ilu California..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn gba tó padà sí South Áfríkà, ó gba iṣẹ́ Vir Die Vols, ipa rẹ̀ nínu eré yí ló jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ TallGrass International Film Festival.Ní ọdún 2017 ó bẹ̀rẹ̀ ilé iṣẹ́ fún eré ṣíṣe tirẹ̀ tí ó pè ní Art of Acting South Africa.Igbeyawo ní ọdún 2018, ó sọ wípé òhun àti andries Levi Pretorius fẹ́ ara wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe igbeyawo ni ọjọ́ kẹta lélógún oṣù kejì, ọdún 2019.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Moitgeri pheto (Bii ni ojo Kọkànlá osu karun-un odun 1981) je osere ni orile ede South Afrika, o gbajumo fun ipa Miriam ti o ko ninu ere Ttary leyin farahan ninu ere T&eisi, pheto ti kopa ninu oríṣìíríṣìí ere miran bii Wch a Fire(2006), Goodbye Babe (2007) ati How to tọ́jú 2 million (2012).Ni osu keje odun 2008, oun ni o se oju fun l'Ore..
wikipedia
yo
Nandi Nyembe (Bii ní ojo kokandinlogun osu kejo odun 1950) je osere ni orile ede South Afrika ti o gbajumo fun ipa ti o ko ninu ere Zone 14 ati Soul City.Igbe pepe aye re won bii Nyembe si ilu GLiptown ni orile ede South Afrika ni odun 1950, o si ti gbe ni awon ilu bii Botswana, East London ati South Afrika nigba ti o si kere..
wikipedia
yo
Nyembe sọ wí pé wọ́n ma fi ohun ṣe ọmọ ọ̀dọ̀ nínu eré nítorí pé òhun jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀.Iṣẹ́ Nyembe gbajúmọ̀ fún ipa NANdi òpòyè tí ó kó nínú eré Zone 14..
wikipedia
yo
Ó ti kópa nínu àwọn eré bíi Rebe Man (1999), Saturday Night at the Palace (1987) àti Yesterday (2004)..
wikipedia
yo
ní ọdún 2007, ó farahàn gẹ́gẹ́ bí Thembe Makrake nínú dírámà tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Jacob's Cross..
wikipedia
yo
Àwọn máa tí ó tún kópa nínú wọn nii Itane and Stones, Ashes to Ashes.Àṣàyàn àwọn eré tí ó ti soon Oriwe Oriwén Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mike ayọ̀bámi bámiloyè ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtala oṣù kẹrin ọdún 1960..
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí eré, olùgbéré-jáde Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ajíyìn-rere tí ó ma ń lọ eré oníṣe láti fi jèrè ọkàn àwọn ènìyàn, ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ àti Ààrẹ Mount Zion Faith ministries àti ti Mount Zion Television.Ó sì tú jẹ́ ọ̀kan lára Ìjọ Christ Apostolic Church.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọ́n bí Mike ní ìlú Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 1960.Ìyá rẹ̀ kú ni nígbà tí ó wà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin..
wikipedia
yo
Felicia Adepoju Adesanya ni o tọju rẹ titi o fi dagba ki o to le moju to ara rẹ..
wikipedia
yo
O keko ni ile-eko diVisional Teachers' Training College ni ilu Child-Module..
wikipedia
yo
Ó dá ìjọ Mount Zion ní ọjọ́ karùún oṣù kẹrin ọdún 1985..
wikipedia
yo
Eré tí ó gbé jáde ní Hell in Conference ni wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ ní National Christian Teachers Conference ní ọdún 1986 ní ìlú Ileṣa ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun .Ó ti kópa, darí àti gbé àwọn eré ìru-ó-tutọ́ jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn.Ìgbésí ayé Rèré inú oṣù kẹjọ ọdún 1985, ìyàwó rẹ̀ Arábìnrin Gloria bámilóyè gbà láti jẹ́ aya rẹ̀, èyí ni ó sì bẹ̀rẹ̀ ipilẹ̀ ijó wọn (Mount Zion)..
wikipedia
yo
Wọ́n bí àwọn ọmọ mẹrin (Damilola, Joshua, and Darasimi Mike-Soba).Àwọn ìtọ́kasíe tún le wòlĩst of Yorùbá Peopleàwọn Ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1960àwọn Ènìyàn Alààyè, Malé film Actors-Century Nigerian Malé ActorsYorùbá Mago Actors From From IleshaNigerian Christian clergyYorùbá Christian clergyPeople From Osun..
wikipedia
yo
Ada Ameh jẹ́ òṣèré ará ìlú Nàìjíríà kan tí ó ti lò ju ọdún ogún lọ ní ilé-iṣẹ́ fíìmù ti Nàìjíríà àti pé ó ṣe àkíyèsí jùlọ fún ipa rẹ̀ bi Anita ní fiimu 1996 tí àkọlé rẹ̀jẹ́ “ Domitilla” àti bi Emu Johnson nínu eré aláakẹkọ-ẹ̀ye ti àkọlé rẹ jẹ́ Johnsons ..
wikipedia
yo
Ameh nínu The Johnsons ṣe ìfihàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn òṣèré Nollywood mìíràn bíi Charles Ijiejie, Chinedu Ikedieze & Olumide Oworu .Igbesi aye ibẹrẹ ati Eko Ameh, Bótilè o jẹ́ abí̀ ti Idoma ni ìpínlẹ̀ Benue, a bí tí o si dàgbà nii Ajegunle ní ìpínlẹ̀ Eko, apá iha Ì-oòrùn gúùsù Ì-Ogún ti Nàìjíríà tí o bori púpọ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn tí ń sọ èdè Yoruba ti Nigeria ti Nigeria..
wikipedia
yo
Ameh gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé alakọbẹrẹ àti ilé-ìwé gíga ní ìpínlẹ̀ Èkó ṣùgbọ́n óò parí ilé-ìwé Ọjọ́-orí 14.Iṣẹ́ Ameh ní ọdún 1995 ní Ìfọwọ́sí apákan ti ilé-iṣẹ́ fiimu ti Nollywood àti gba ipò fíìmú àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1996 níbití ó ti kópa bi Anita ní físán “Domitila” Fíìmù kan tí ó di iṣẹ́ àṣeyọrí ..
wikipedia
yo
Fíìmù náà ṣe àgbékalẹ̀ àti ṣe ìtọ́sọ́nà nípasẹ̀ Zeb Ejiro ..
wikipedia
yo
Ameh tún ṣe ìfihàn nínu jara TV tí Nàìjíríà tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ The Johnsons èyítí o tún di iṣẹ́ àṣeyọrí tí ó gba àwọn àmì-ẹ̀rí .Ìgbésí ayé ara ẹni Ameh ní ọmọ obìnrin kan tí ó bí ní gbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá..
wikipedia
yo
Ameh jẹ́ ẹnití ó n sọ èdè míràn àti èdè abínibí agbègbè rẹ̀ ní èdè Idoma, Gẹ̀ẹ́sì, Yorùbá nsọ ọ̀pọ̀ èdè àtioen ọdún 2017 wọ́n gbé àkọlé olórí fún Ameh ní ìpínlẹ̀ Bénuòmìnirasíra tí àyán yọ Domitila Aki na Ukwa (pẹ̀lú Osita Iheme & Chinedu Ikedieze) Phone Swap (pẹ̀lú Wale Ojo, Chika Okpala, Nse Ikpe-Etim & Joke Silva)Blood Money'Atlas Oloture Oloat Husbandking of Shitta Must Gori Million baby Good Turn Trouble’’ Telifisonu tẹlifíṣọ̀nù The Johnsonṣàkópọ̀ Ìtọ́kasí awọn Ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Zineb ohùn (; ti a bi ni odun 1980) je osere ede French ti owa lati ilu Morocco, o je olokiki fun ipa re ninu jara ede Faranse titi Nadia el Mansour, ti akole re je the Bureau..
wikipedia
yo
Wọ́n bi Zineb ẹ̀yẹ ni ọdún 1980, ni Ilu Morocco, ó lọ si ilé ẹ̀kọ́ elédè Faranse ni bi ti oti ko ìmọ̀ ere ori itage àti ijó..
wikipedia
yo
Ni igba ti o pe omo odun medogun, o lo si ilu pariṣi gba oye-oye ni Eko oselu lati owo McGill University ni ilu Kánádà..
wikipedia
yo
O se ise pelu un, ni New York ni odun 2003 o gba oye masitas ninu eto oselu lati Sorbonne University ni ilu Parisi, lehin na ogba oye mastas imiran ninu iṣelọpọ ni Paris.17 bere ise osere ni kárakára lati odun 2009, pelu ipa kekere ninu ránṣẹ́ ati The Misalẹ́rìí of Franck and Martha..
wikipedia
yo
I pa akoko ti oko ninu ere Deux Fenetres in 2013 ati La Marche verte (2016)..
wikipedia
yo
Amal Ayouch (ti a bi ni odun 1966) je osere ilu Morocco, ati odun 1990 ni o tin se ere, lori itage ati ninu fiimu pelu ede Faranse..
wikipedia
yo
ní oṣù kìíní ọdún 2015, wọ́n fun ní àmì ẹ̀yẹ àpọ́nlé ní àyájọ́ àwọn obìnrin òṣèré tí ó wa yẹ ní Brazzaville Ayouch ti kópa iwájú nínú Morocco's Fondation des arts Vivants (Ìpìlẹ̀ àwọn àwòrán tí ó ń gbé)àwọn ère rérémáa ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyẹ̀àwọn Ọjọ́ìbí ní 1966..
wikipedia
yo
Francis Odega je osere elefe omo orile-ede Naijiria, ti o ma n se awada, ti o si ti gba ami-eye fun awada lori fọ̀ràn fidio re ti o gbòde kan lori ẹ̀rọ ayelujara..
wikipedia
yo
Òun ló ni ètò night of a thousand laughs tí ó wà fún pípa àwọn eniyan léríin..
wikipedia
yo
Francis gba ami-eye "Best Actor" oun pelu HLoilla Danda fun osere ti o peregede julo julo "Best African Colla" ni odun 2013 Ghana Movie Movie 2013..
wikipedia
yo
Francis di ìlú-mọ̀ọ́ká lẹ́yìnnti ó kópa nínu eré back from South Africa ti gbajú-gbajà olórin 50 cent àti Atie Tenh ti kópa..
wikipedia
yo
Lára ipa tí ó kó ní bí ó ṣe ń sọ èdè Amẹ́ríkà nínú ẹ̀fẹ̀ rẹ̀.Àwọn àṣàyàn fíìmù tí ó ti kópaback from South Africahouse of Goldbaby Policehow Far?Romeo Without Julietmoney for Handoòẹwàa in Londonmy last wedding cultere àtìgbàdégbàclinic mattersáwọn ìbáṣepọ̀ rẹ̀lẹ́yìn tí fìdí rẹ̀ di ìlúmọ̀ọ́ká , Francis tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ Etisálàt gẹ́gẹ́ bí aṣojú wọn.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ìtàkùn ìjásódeàwọn ènìyàn alààyèmale Actors From Delta StateAmbrose Alli University Alumníní Magone film Actors -Century Nigerian male Actors-21st Nigerian Malelé Actors Coce Year of Birth Missing (Living People)..
wikipedia
yo
DeOlinda Ines Caẹtano Olofin (ti a bi ni ọjọ kankanla osu karun odun1995) je omo ilu Angola ti o je akorin ati osere.org ilu Luanda ni won bi Olofin si, sugbon odagba ni Ingombota..
wikipedia
yo
O so wipe ohun lo igba omode ti odun, ati pe ati kekere ni toi feran orin..
wikipedia
yo
Awon ti Oman wo awokose won ni Phyllis Hyman ati Selena Quintani..
wikipedia
yo
Ilu Tanzania ni o gbe gegebi owe, nitori o ni egbon obinrin ti on sise ni ile ise asoju Angola..
wikipedia
yo
O ko lo si Guimaraes, ni ile Portugal lati ni ojo iwaju ti o dara..
wikipedia
yo
Oríd kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin ní Porto.Ní ọdún 2016, ó borí nínu ìpele kẹta títí The Voice Portugaltí ó waye ní CD, wọ́n tún pè ní Whitney Houston titun nítorí ọkọ Orin Whitney Houston, I Have Nothing..
wikipedia
yo
Ótún kọ orin "I will Always Love You" ti Mariah Carey kọ ati "A moment Like This" ti Kelly Clarkson ní igbeyin ìdíje na..
wikipedia
yo
Ohun ati iya eh tunyá lẹhin ti won wa ni yiya fun ọdun meji.Ni tori oje olubori idije yi, o ṣe ifowobowe pẹlu Universal..
wikipedia
yo
Ni osu kewa odun 2016, o ko ipa ninu eto "dent".orin akoko eh je "Primeira vezls" ti ojade ni osu kewa odun 2016 ni osu kankanla odun 2017, o fi awo orin re kale, eyi ti akori re je oruko e.Awo orin yi gba irawo meta ati abo ni owo sabado, o gbe ori yin fun Kimakẹ́kọ̀ọ́meric fun awon ise takun takun ti ose lori awo orin na..
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, Model àti Olóòtú ètò.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Mélòó International School àti Mount Saint Gabriels Secondary School..
wikipedia
yo
Ó jáde ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti Benue state University nínu ẹ̀kọ́ mpọ́.Ó kópa gẹ́gẹ́ bí Olú-ẹ̀dá ìtàn nínu soap opera ti Tinsel tí ó aì tún ti kópa nínu eré Àgbòmọ́ gbọ́mọ Express and the Wages.Ajibade wọ́n Most Outstanding Actor/Model of the Year at the 2011 Nigerian Model Achievers Awards.Personal Life was Married to Actress oSass Ighoside, Together, they India One Daughter, azarí Tiwa Osaru Ajigu.Àwọn fíìmù rẹ̀ gbọ́mọ Express Express (2015) 30’s (2015) The Wages (2013) twisted Thorne (2011)Àwọn ère orí t.V Tinsel (2008-See) alsolist of Yorùbá People Ìtọ́kasí àwọd Official Official àwọn ènìyàn Alààyè Alààyè Film Actors Kimba Television Actors Actors Models Models– Dodu Acwed-21st Nigerian Mago Actors Onídàájọ́ Stubs Kan Ìbéèrè Àjàpá Mols Mals State University Aludọ́gba-Century From From From Eper of Birth Missing (Living People)..
wikipedia
yo
Heloísa Jorge (ti won bi ni ojo kini osu keje odun 1984) je osere ati oludari ere ti o wa lati ilu Angolaìgbésíayé won bi si Chitato ni Lunda Norte Province..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Brasil ìyá rẹ̀ sì wá láti ìlú Angola..
wikipedia
yo
Ojuwe ara e gege bi eyan kan ti oju man ti ni igba ti owa ni omode.Ni igba ti o wa ni omo odun mejila ohun ati awon molebi re ko lo si ilu Brasil nitori Ogun Abẹ́lé Angola, win gbe ni ilu Montes Claros..
wikipedia
yo
Jorge bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Thearter ni Ile Eko, Osi Darapọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ wan..
wikipedia
yo
Ni igba ti o se idanwo ati wole si ile eko giga Brasil ni omo odun mejidinlogun, o gbero lati ko eko sise aworan..
wikipedia
yo
O ko lo si ilu Salvador, Bahia lati lọ si ile eko giga titi bahiani igba ti on ko eko ere ori itage, Jorge bere si ni ko awon iwa Ìrònú awujo osi fi kun igberaga ara eni ti ti ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007 wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Braskem nítorí ipa rẹ̀ nínu eré O Didia 14, Angelo Flávio ni ó darí eré na..
wikipedia
yo
Pẹlu ni ọdún 2007, Jorge kó èrè Uma Mulher vestida dé Sol, lati bu iyi fun ariano Suasasbero ja de ile eko giga ni ọdun 2008..
wikipedia
yo
Ni odun 2009, wan tun fi oruko Jorge kale fun ami eye Braskem fun ipa re ninu A Farsa da Bomber Preguica, ti oludari re je Hrildo Deda..
wikipedia
yo
O pada si Angola ni odun 2009 pelu egbe itage e, won se ere Amesa ti José Mena Abrantes ko.Ni odun 2012, Jorge ko ipa Fabiana ninu jara ti akori e je Gabriela..
wikipedia
yo
Wọ́n pè ki ó wá dara pọ̀ mọ́ jara Angola Dikulumes, eleyi ti o ṣe agbega fun àwọn eniyan aláwọ̀ dúdú ni ọdún 2014..
wikipedia
yo
Ni ọdun kan na, Jorge ṣe alejo eto Globo International Connections program..
wikipedia
yo
O tun ko ipa iya ti ọfẹ ku ti orukọ rẹ jẹ Gilda Cunha Matheus ninu jara A dona do pedaco.Awon aṣayan eretẹlifisiọnuawọn fiimuawọn itọkasiawọn ọna asopọ ita Heloisà Jorge at the Internet Movie database.Awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1984..
wikipedia
yo
Lucrecia Paco (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kewa odun 1969) je osere ti o wa lati ilu Mozambique..
wikipedia
yo
O je okan larin awon osere ti oniyi ju ni Mozambique.ìgbésíayé Paco dagba ni Maputo..
wikipedia
yo
Ni igba ti owa ni omode, o feran ki oma ko orin ati ki o ma jo si awon orin ibile, eleyi ti ko po níta ki Mozambique to gba ominira ni odun 1975..
wikipedia
yo
Ko da wan Paco ni ile iwe nitori o man so ede ibile..
wikipedia
yo
Lehin ominira awon egbe sosialisiti gba won ni iyanju ki won ma se ere itage ati bebelo, Paco si kopa ninu ijo, orin ati ewi kika.Ni asiko Ogun Abele Mozambique, Paco fi akiyesi eh si ara ere itage gege bi ise oselu..
wikipedia
yo
Ni odun 1986 Paco wa lara awon oludasile Mutumbela Taye Trourou, egbe ere itage akoko ni Mozambique, ti osi wa di eni..
wikipedia
yo
Awon ere Soviet ti owo lo wu lori Ìpèsè se awon ere kukuru nipa bi o se ri ki eyan ma gbe ni Mozambique..
wikipedia
yo
Kí wọ́n bá lé ṣe olùgbòwọ ẹgbẹ́ eré ìtàgé na, wọ́n kó ilé iṣẹ́ ìlạ̀.[Paco fun ra e ni isnmí ọdún marún nítorí pé ó re ní ọdún 2009 Instituto Itau Cultural pé Paco wa sí ìlú Brasil..
wikipedia
yo
O ko ipa ninu project antidote pelu ere Mulher Asfalto..
wikipedia
yo
Ni odun 2009 mu Paco gege bi olukopa ninu ere Quero Ser uma Elala..
wikipedia
yo
Lehin igba na oko ipa kan ninu nineẹ̀fọ́ ere Ibra akoko titi Mozambique.Awon eretelefisonufiimuawon itọkasiawon ona asopo ita lucrecia Paco at the Internet Movie databaseawon eniyan apapoawon Ọjọ́ìbí ni 1969..
wikipedia
yo
Chinyere Yvonne Okoro je osere omo Naijiria ati Ghana..
wikipedia
yo
Okoro je omo mewa pupo, nitori eyi ni ofin man pe ara re ni omo Afrika..
wikipedia
yo