cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó lo ọdún mẹ́wàá àkọ́kọ́ ayé rẹ̀ ní ìlú Benin ṣáájú kí ó tó kó lọ sí ìlú Àbújá.. | wikipedia | yo |
O ni eto ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ ní Ile-iwe Our Ladies of Opààlà Private School, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Queen's College ní ìlú Èkó ṣaájú kí ó tó kọ́ ẹ̀kọ́ Economics ní Yunifásítì ìlú Abuja.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Okujaye tí n ṣiṣẹ́ fún àìmọye ọdún ní orí ìpele ṣaájú ìfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ní Nollywood.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹbi alaye rẹ, ifihan rẹ ni Amstel Malta Box Office ṣe ifilelẹ iṣẹ rẹ, o si sokun fa ipa akọkọ rẹ ninu fiimu Alero Symphony.Awon itọkasi awọn eniyan Alààyèawọn Ọjọ́ìbí ni 1987awọn oṣere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oloye Oyinsola Abayomi, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí "Oyinkan"kan ni wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1897, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹta ọdún 1990 jẹ́ Àjàjàòmìnira àti àṣegbéfàbọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni adarí ẹgbẹ́ obìnrin, Girl Guides àti olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́-òṣèlú àwọn obìnrin, Nigerian Women's Party, NWP.Igba Ewe àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dún bí Ó gẹ́gẹ́ bí Oyinkansola àjásà lọ́dún 1897 ló rílé-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ ló máa ń pè é ní oyinkan, èyí tí ó jẹ́ àìkúrú orúkọ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Orúkọ Bàbá rẹ̀ ni Kitóyè àjásà, Ọmọ bíbí Yorùbá pọ́nbele, ẹni tí ìṣèjọba Bìrìtì ́ko kọ́kọ́ fi joye alàgbà ìjọ.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ ni Lucretia Olayìnìnka Moore, ọmọbabìnrin ìlú Ẹ̀gbá.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé ní ilé-ìwé àwọn obìnrin, Anglican Girls' Seminary ní ìlú Èkó lórílẹ̀-èdè Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
Bákan náà, ó kàwé gboyè lọ́dún 1909 ní ilé-ìwé Young Ladies Academy ní Ryford Hall, tí ó wà ní Gloucestershire,ní orílẹ̀-èdè Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1917, ó kàwé ní Royal Academy of Music ní ìlú London.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olùkọ́ ìmọ̀ orin ní Anglican Girls' Seminary.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò yìí ni ó pàdé ọkọ rẹ̀, tí orúkọ rẹ̀, amo Mórọ̀n Abayomi tí wọ́n sin fẹ́ ara wọn lọ́dún 1923.. | wikipedia | yo |
They married in August 1923, tí wọn yóo pa nílé ejò lẹ́yìn oṣù meji sí ìgbà náà.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Adebukola Oladipupo (ti a bi ni Oṣu Kaàrún Ọjọ 23, Ọdun 1994) jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria kan ti o bẹrẹ ere ṣiṣe rẹ ninu ere MTV Shuga .Ìgbé ayé rẹ a bi Oladipupo ni Ilu Lọndọnu ṣugbọn o ni ẹtọ ẹkọ rẹ ni Ilu Eko.. | wikipedia | yo |
Oladipupo lọ si ile-iwe alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Bellina Nursery and Primary School, Àkoka, Ilu Èkó.. | wikipedia | yo |
O tun lọ si ile-iwe Babcock High School ati Caleb International School fun eto-ẹkọ girama rẹ.. | wikipedia | yo |
O keeko giga rẹ ni Covenant University nibi ti o ti ko awon eko ere itage lẹgbẹẹ imo isakoso.. | wikipedia | yo |
O ṣe idanwo ni aṣeyọri fun MTV Shuga ni ọdun 2015 nibiti wọn ti fun ni ipa “Faas.. | wikipedia | yo |
O tọ́ka sí mo Abudu tó kọ̀ láti ní igbagbọ ninu ara rẹ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ṣe pàtàkì fún àṣeyọrí náà.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2015 o ṣe afihan ninu apa kinni indigo, inevitable ati the other me.. | wikipedia | yo |
Ni odun 2017 o kopa ninu fiimu Missing.Awon fiimu ti o ti ni lorukọ rẹ kun Moms at War, Phases (NdaniTV), The Men's Club, ati Africa Magic Forbidden.Oladipupo je okan lara awon ti won si n kopa lowo ninu MTV Shuga nigba ti ere naa din ku si ere oníṣókí ti won pe akole re ni MTV Shuga Alone Together, eyi ti n se alaye awon iṣoro coronavirus ni Oṣu Kẹẹ̀rin Ọdun 2020.. | wikipedia | yo |
Eré náà jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ fún ọgọ́ta àṣálẹ́, àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ sí pẹ̀lú Àjọ Ìlera Àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Eré náà dá lóri Nàìjíríà, Gúúsù Áfríkà, Kenya àti Côte d'Ivoire àti pé ṣíṣe rẹ̀ wáyé pẹ̀lú ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àwọn olùkópa eré lórí ẹ̀rọ ayélujára.. | wikipedia | yo |
Gbogbo yíya àwòrán eré náà sì waye latọwọ àwọn oṣere fúnrawọn.. | wikipedia | yo |
Lára wọn ni Jemima Osunde, Lerato Walaza, Sthandiwe Kgoro, UzoAmaka Aniunoh ati Mohau Cele.Awon Ìtọ́kasí àwọn oṣere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ọ̀rọ̀-iṣẹ́ ni òpómúléró, tàbí kókó ọ̀rọ̀ inú gbólóhùn èdè Yorùbá .. | wikipedia | yo |
Olori Kofoworola Ademola ti a tun mo si Kofoworola Aina Ademola ati arabinrin Ademola ti o gboye order of the British Empire, (mbe), MFR, OFR ni won bi lọjọ kokanlelogun osu karun-un odun 1913, ti o sin ku lọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún osu karun-un odun 2002 je olukọ ọmọ Naijiria oun ni aare akoko ti ajo ẹgbẹ obinrin, National Council of Women Societies lórílẹ̀-ede Naijiria, oun naa sin ni adari egbe obinrin naa lati odun 1958 si 1964.. | wikipedia | yo |
Oun ni obinrin Adulawo akoko ti o kawe gboye digírì ni Oxford University bakan naa, o je onkowe awon omo.aye rẹwọn bi ṣègbọràn si ebi amofin ati ọmọba Eric Orelu Moore ti ilu Egba, pelu aya re, Aida Arabella, ti o je omo Scipio Vaughan ati iran Cherokee.. | wikipedia | yo |
O jẹ ibatan oyinkansola Abayomi ati olori Charlotte Obasa.. | wikipedia | yo |
Ó lo idaji ìgbé-ayé rẹ ni ẹ̀kọ àti ìlàjì tó kù ní United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Girls School, ní ìlú Èkó; Vassár College, ní New York; Portway College, ní ìlú Reading, àti St.. | wikipedia | yo |
O kawe gbawẹ eri dìgírì ninu imo olukọni ati ede Gẹẹsi ni Yunifasiti Oxford, nigba ti o wa ni Oxford, o kọwe itan olójú-ewé mọ́kànlèlógún nipa ìgbé-ayé MarGátì perham lati ṣe atako asiko iwe itan àwọn Òyìnbó nípa Afirika, o kọ nipa itan igba ewe rẹ gẹ́gẹ́ bí i àmúlùmálà àṣà ìbílẹ̀ àti òkèèrè.Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé kò sọ nípa ìwà elẹ́yàmẹyà tí wọ́n hù sí i nígbà tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n, ó fi ibinu àwọn ìwà yìí hàn nígbà tí wọ́n bú u ní oríṣiríṣi èébú elẹ́yàmẹyà.. | wikipedia | yo |
Kofoworola pada si Naijiria lọ́dún 1935 ti o sin gba iṣe olukọ ni ile-iweQueens Queens College ni ilu Eko.. | wikipedia | yo |
Nígbà tó wà ní Èkó, ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹgbẹ́ obìnrin pàápàá jùlọ YCP.Lọ́dún 1939, ó fẹ́ Ọmọba AdeTokunbo Ademola, òṣìṣẹ́ ìjọba lọ́lẹ̀, wọ́n sìn bímọ marún-ún gẹ́gẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìyàwó Ọmọba Yoruba, ó ní pàmọ̀ sí ìgbẹ́-ayé Olorì, àti pàfà, òun fún ara rẹ̀ jẹ́ Ọmọba, ṣùgbọ́n pé ọkọ̀ rẹ̀ jẹ́ alàgbà ìjọ ijo, ló fa a ti ń fi ń pè ẹni Iyaafin Ademola, tí gbogbo ènìyàn mọ́ ò mọ̀. tí gbogbo yá, iṣẹ́ gbe ọkọ̀ rẹ̀ lo sí ìlú Warri rẹ̀, gbogbo àwọn ìlú wọ̀nyí ní kọ́ ń kóbí ti kọ́ ní ó pọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ obìnrin.. pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ obìnrin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe àtẹ̀jáde Ìwé-ìtàn Ìgbésí-ayé kòfoworola Ademola àti àwòrán gbémìji Rosiji tí wọ́n pè ní Portrait of a Pioneer lọ́dún 1996.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
PEGGY Ovire Enoho tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Peggy jẹ́ olùgbéré-jáde, òṣèré àti Modeeli ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà òun ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún "òṣèrébìnrin tí ọjọ́ iwájú rẹ̀ dára jùlọ ti (English)" níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ti ọdún 2015.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀órin jẹ́ ọmọ ìlú Ughellilli ní Ìpínlẹ̀ Delta, amo wọ́n bí sí Ìpínlẹ̀ Èkó òun ní Anilẹ̀ àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ìlú Itire ní agbègbè Surulere àti Ile-ẹkọ oniwe mẹ́wàá ti Angundeen ní ìlú Surulere kan náà ní Ìpínlẹ̀ Èkó ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìpínlẹ̀ Delta tí ó wà ní ìlú (ábráka), àmọ́ tí kò parí níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó padà sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ambrose Alli láti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ okòwò àti ìṣúná.Iṣẹ́ rẹ̀ṣáájú kí Ovire tó di ìlú-mọ̀ọ́ká nínú Nollywood, ó ti kọ́kọ́ ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Modeeli.. | wikipedia | yo |
Ovire ṣe alaye ninu ìfọ̀rọ̀nwanilẹ́nu wo kan pẹlu iwe-iroyin Yhe puch wipe ere oun akọkọ ni Uche Nancy gbe jade .. | wikipedia | yo |
O dinlaami-laaka ninu ise re gege bi osere nigba ti o kopa ninu ere àtìgbà-dègbà onípele ti akole re n je Husband of Lagos ti won ma n ṣafihan re lori awon ero amo-máwòrán ile Naijiria.Awon ami-eye ati ÌFISỌRÍire gba ami-eye ti òṣèrébìnrin ti ojo iwaju re dara julo ni odun 2015 ninu ayeye City People Entertainment Awards.Àwọn eré tí o ti gbe jadeyato si wipe o je osere, Ovire tun je olùgbéré-jade ti o si gbe awon ere bi Ufuoma, Fool Me Once, ati The other woman woman jade.Àwọn aṣayan ere ati ere oribero amo-máwòrán a long Night ìkọ̀sẹ̀game Changer of Lagos (TV series) with heart heart me Yes or Nothe Apple of Discord Last Garwọnú Chances(2014) gege bi loladéàwọn awon irin ìjásóde Peggy ka 2016 IMD page odun alààyèNigerian Actors-21st Nigerian Actors of Birth Missing (Living People).. W).. | wikipedia | yo |
Charlotte Olajumoke Obasa ti orúkọ olùdarí rẹ̀ n jẹ́ Spanishze, ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje Oṣù Kìíní ọdún 1874, tí ó sin kú lọ́jọ́ kẹtàlélógún ọdún 1953 jẹ́ gbajúmọ̀ àfọwọ́ṣàánú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Blaize ati iyawo rẹ ti o je oniwosan oriṣadipé Obasa.I-aye rẹCharlotte Olada Obasa jẹ ọmọ Saró ti won bi si idile gbajumọ oṣelu ati oloro, Richard Beale Blaize ati Aya Re, Emily Cole Albertze | wikipedia | yo |
O lo igba ewe rẹ ni Ilu Eko, nibi ti baba rẹ ti jẹ oludasile iwe-iroyin ti wọn pe ni The Lagos Times and Gold Coast Colony Advertiser ati the Lagos Weekly Times.. | wikipedia | yo |
O kọ́kọ́ kàwé ní ilé-ìwé Anglican Girls' School ní Èkó,lẹ́yìn náà, o sọdá lọ kàwé sí i lókè òkun lórílẹ̀-èdè England lọ́dún 1902, ó fẹ́ ọmọba Saró, ọmọba Òrìṣàdipé Obasa.. | wikipedia | yo |
Odidi ilé tuntun ni baba rẹ̀ fi fún wọn ní ẹ̀bùn igbeyawo.. | wikipedia | yo |
O je ibatan kofoworola Ademola Olajumoke jẹ onisowo ati Parakoyi afowo to saaju ija fun eto ati ikawe omo obinrin.. | wikipedia | yo |
Nitori akitiyan rẹ ni wọn fi da ile-iwe awon obinrin ti won pe ni Lagos School for girls ti o wa di Welẹ̀yàn girls' High School sile lodun 1907, lori ile ti o ya won.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1913, ó ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ awakọ̀ àkọ́kọ́ sílẹ̀ ní ìlú Èkó tí ó pè ní ànfàní Bus Service, nígbà náà, ó ní ọkọ̀ àjàgbé mẹ́ta, ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tááṣì mẹ́ta àti ọkọ̀ èrò, bọ́ọ̀sì mẹ́fà kí ó tó di ọdún 1915.Lọ́dún 1914,ó wà lára àwọn tí wọ́n dá Ẹgbẹ́ Ògbóni ìgbàlódé Reformed Ògbóni Fraternity sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó kọ́kọ́ joyè ìyá abìyẹ́ nínú ẹgbẹ́ náà lọ́dún kan náà.Ó ta tẹrú nípàá lọ́dún 1953.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kenneth obìnna ọkọlie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún osù kẹjọ ọdún 1984, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, Modeeli tí ó sì ti fìgbà kan jẹ́ ọ̀gbẹ́ni Nàìjíríà nígbà kan rí látàrí ipa rẹ̀ nínú iṣẹ́ Modeeli ní ọdún 2010.. | wikipedia | yo |
ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ ti ayẹyẹ City People Entertainment Awards gẹ́gẹ́ bi òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ ti o peregedé jùlọ ní ọdún 2015Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀okolie jẹ́ ọmọ bíbí ìlú híhi ní ìpínlẹ̀ Anambra.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé jáde nílé ẹ̀kọ́ Valley View University ní orílẹ̀-èdè GÁNÀ.iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré àti Modeeliṣáájú kí okolie tó di ìlú-mooka nínú ilé-iṣẹ́ Nollywood, ó ti bẹ̀rẹ̀ bí Modeelieli.ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
O ṣe alaye wipe sise Moderaeli kii se ohun ti o wu oun lati okan wa nitori wipe oun sin ore oun kan lo si ibudo ifihan naa ni ki wọn to fi iṣẹ naa lọ oun ti oun si gba lati sise naa.. | wikipedia | yo |
Oun yege ninu ifihan naa ti wọn si yan oun lati kopa ninu idije ni ọdun 2006.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó tún kópa nínú ìdíje tí ó mú gba àmì-ẹ̀yẹ ọ̀gbẹ́ni Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Okolie tún kópa nínú ìfihàn okùnrin tí ó dára jùlọ ní àgbáyé, tí ó sì gba ipò kejì.. | wikipedia | yo |
Ó tún dara pọ̀ mọ́ wọn àwọn òsèré orí-ìtàgé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2011.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ọ̀v gba àmì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards fún òṣèrékùnrin amugbalegbe tí ó peregedé jùlọ.Ìgbé ayé rẹ̀ Okolie ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú arábìnrin nwáká Jessica ní ọdún 2017, wọ́n sì bímọ ní ọdún 2019.ìjínigbé ti ọdún 2012ọkọ̀ rin ìrìn-àjò lọ sí ìlú Owerri tí ó jẹ́ Olú-ìlú fún ìpínlẹ̀ fún ìpínlẹ̀ láti lọ ya sinimá kan pẹ̀lú àwọn òṣèré akẹgbẹ́ rẹ̀ kan ń Sylvls.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fi lédè wípé àwọn ajínigbé jí okolie àti Nkírú Sylvanus gbé ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kejìlá, tí wọ́n sì ń bẹ̀rẹ̀ fún ọgọ́rùn ún mílíọ̀nù (N100,000,000) kí wọ́n tó fi àwọn òṣèré méjèèjì yí sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn ajínigbé náà dá okolie àti ẹnìkejì rẹ̀ nkírú Sylvanus sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ kẹfà tí wọ́n ti jí wọn gbé ní déédé agogo mẹ́wàá àbọ̀ alẹ́.. | wikipedia | yo |
Àmọ́ iye tí àwọn ajínigbé náà gbà kí wọ́n tó dá wọn sílẹ̀ kò hàn sí ẹnikẹ́ni.Àwọn Àsàyan eré ReTV Showṣàwọn ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn ìjásóde Àwọn Ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1984Nigerian Actors-21st Nigerian Actorsígbó Malé Actors Malé Modelsígbó Maete Models.. | wikipedia | yo |
Olatokunbo Susan Olasobunmi Abeke Olagundoye (ti a bi ni 16 osu Kẹẹ̀sán odun 1975) je oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ bi Hayley Shipton nínú Castle àti Jackie Joyner-Kersee nínu eré aláwàdà ABC TV kan tí a mọ̀ sí The Joperborsipẹpẹ ayé rẹ̀ a bí OlatoOlatod Susan Olasobunmi Abeke Olagundoye ní ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Norrwe tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó ní ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Nàìjíríà, Swítsàlandì, àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ó gba oyè-ẹ̀kọ́ ní ìtàgé láti ilé-ẹ̀kọ́ Smith College.Iṣẹ́ iṣẹ́ Olagundoye ṣe ìfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lójú amóhù-máwòrán fún ti eré tẹlifíṣọ̀nù àti sinimá àgbéléwò ní ọdún 2002 nínú eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Education of Max Bckford; àti fíìmù Brown Sugar.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, ó kópa nínu eré orí ìpele kan, Saint Lucy's Eyes, ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ruby dèé.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2005, ó ṣe ajọdasilẹ ilé-iṣẹ́ ìtàgé kan tí wọ́n pè ní Three chicks Theatre, èyítí ó ṣe àgbéjáde eré Andrea Ppcio Kan, One Nation Under ní ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
Àwọn fíìmù míràn tí ó ní lórúkọ rẹ̀ pẹ̀lú A Beautiful Soul, Come Back to Me, Abve Trust àti The Salon.Ni ọdún 2012 Olagundoye jẹ́ olùkópa Dede nínú eré aláwàdà ABC kan The Neighbors, níbi tí ó ti kó ipa Jackie Joyner-see títí di ìgbà tí eré náà fi jẹ́ fífagilé ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Olagundoye darapọ mọ awọn olukopa ti ere alawada ti ABC kan, Castle ni ọdun 2015 gege bi olukopa deede fun ipa ti Hayley Shipton.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1975awon osere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Eyi ni atojo awon obinrin agbaboolu-afẹsẹgba omo Naijiria loke okun ti won ti gba boolu-afẹsẹgba fun oko agbaboolu obinrin ti Naijiria lati odun 1991.Àwọn agbabooluàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Nkírú Sylvanus tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù Kẹrin ọdún 1982, jẹ́ òṣèré àti olóṣèlú.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu eré tí ó tó ìgúngún tí ó sì ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards fún òṣèré léwájú tí ó peregedé jùlọ nínú ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ kòpò bí Sylvanus ní ìlú Osìoma, ní Ìpínlẹ̀ Áááánù.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tí Ohabiam àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ní agbègbè kan náà.. | wikipedia | yo |
O si lo si ile-eko fasiti Gbogbonìṣe ti Ipinle Enugu ti o keko gboye ninu imo ìbára-eni-soro.ise re gege bi oseresvvanus bere ere sise ni dédé omo odun metadinlogun ni odun 1999.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu eré tí ó tó Àádóje.Ó ti fara hàn nínu ìwé-ìròyìn The Guardian's ní ọdún 2017 àti 2018 gẹ́gẹ́ bi gbájúmọ́ jùlọ lórí ìwé-ìròyìn.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèréní ọdún 2011, wọ́n yan an Sylvanus sí ara àwọn ìgbìmọ̀ tí Gómìnà Rochas Okorocha gẹ́gẹ́ bi olùbádámọ̀ràn sí Ìpínlẹ̀ Èkó lórí ọ̀rọ̀ àwùjọ.ìjínigbé rẹ̀ ní ọdún 2012 wọ́n jí Sylvanus gbé ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún Oṣù kejìlá ọdún 2012 tí àwọn ajínigbé náà sì bẹ̀rẹ̀ fún ojú miliọnu naira ( N100,000) gẹ́gẹ́ bi ìwé-ìròyìn Vanguard ti sọ ṣaájú kí wọ́n tó dá wọn sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Mercy Akide Udoh ti won bi oruko kerindinlogbon osu kejo odun 1975 ni ilu Port Harcourt, je agbaboolu-afẹsẹgba obinrin fun Naijiria tele.Igba ewe reMercy si ni ni gba boolu nigba ti o wa lomo odun marun-un pelu egbon re okunrin, selei ati aburo re ipa ni papa ti Papa ti bundu watersideside, lẹ́bàá ogba Harcourtte Harcourt.. | wikipedia | yo |
Láti ọdún méjìlá ni wọ́n ti rí ẹ̀bùn eré sísá rẹ̀ ní ilé ìwé Rosary Secondary School, ní Port Harcourt.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ akópa nínú ìdíje eré sísá eléwahati gùngùn tí ìwọ̀n mítà ọ̀ọ́dúnrún (400), 800m àti 1500m pẹ̀lú àwọn tó jù ú lọ.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà, ó pegedé nínú ìdíje ẹ̀yin orí tabili, ṣùgbọ́n bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ló ti gbajúmọ̀ jùlọ.Mercy gba orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ "Skeh" lédè abínibí wọn, tí ó túmọ̀ sí ọ̀pẹ́lẹ́ńgẹ́ nígbà tí ó máa ń gbá bọ́ọ̀lù pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n jù ú lọ.. | wikipedia | yo |
Lara awon ololufe re ni gbajumo agbaboolu-afẹsẹgba Chidi Odiah, eni ti o n gba boolu jẹ́un fun iko agbaboolu-afẹsẹgba cska Moscow tele.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn àwọn igbìyànjú rẹ̀ ní Port Harcourt, Mercy dèrò Èkó lati tẹ̀ siwaju ninu ẹ̀kọ́ àti bọ́ọ̀lù gbí.. | wikipedia | yo |
Eko lo ti dara po mo iko egbe agbaboolu-afẹsẹgba obinrin awon Omidan Jẹ́gẹ́dẹ́ (Jẹ́gẹ́dẹ́ Babes) pelu iranlọwọ ọmọbabinrin Bola Jẹ́gẹ́dẹ́ise re gege bi agbaboolu-afẹsẹgba 1988 si 1990 Ikọ̀ Me-afẹsẹgba Garden City Queens (Naijiria) 1991-1994 Ikọ̀ Agba-afẹsẹgba Onisánsán (Nàìjíríà (Nàìjíríà) 1995-Naijiria) Taiwo-1998 Ikọ̀ agbabọọlu-afẹsẹgba Ufuoma & 1998– 1998- Me-1999 Ikọ̀ Agba-afẹsẹgba Pelican Stars (Nàìjíríà) 1999-2000 2000 Ikọ̀-afẹsẹgba afẹsẹgba Móábùgan College/ Roads agbairanhas agba-2002 Ikọ̀ Me-afẹsẹgba afẹsẹgba San Diego Spirit 2003- Ikọ̀ Me-afẹsẹgba (afẹsẹgba Rohampton Roeni piranw-W- ↑ Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Destiny Etiko ti won bi ojojo kejila osu kejo odun 1989 je gbajumo òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti gba àmìn Ẹyẹ òṣèrébìnrin tí ó n dàgbà jù lọ ní àgbàlá sinimá àgbéléwò lédè òyìnbó ti city People Movie Award for Most Promising Actress (English) ní City People Entertainment Awards lọ́dún 2016.Ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí kò síko sí abúlé kan tí ó ń jẹ́ jẹ́ údì, ní ìpínlẹ̀ Enugu lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Etíkọ́ kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti gáramá rẹ ní ìpínlẹ̀ náà tí o sin gbàwé ẹ̀rí, first school leaving Certificate àti West African Senior School Certificate.. | wikipedia | yo |
O kawe gbawẹ ẹri dìgírì ninu imọ iṣe Tiata ni Yunifasiti ti Nnamdi Azikiwe University, ni ilu Awka.Iṣẹ Rayotíkò bẹrẹ iṣẹ sinima àgbéléwò lọ́dún 2011.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré nígbà tí ó kópa nínu sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Iitanmili tí gbajúgbajà olóòtú sinimá àgbéléwò, Ernest Obi ṣe lọ́dún, ṣùgbọ́n tí kò tètè jáde títí di ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò náà mú un wà nínú àwọn adije àmì ti City People Entertainment Awards.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó kópa nínu sinimá àgbéléwò Imilimili, Ẹtìko ti kópa ránpẹ́ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn sinimá àgbéléwòàmìn èaṣojúilé iṣẹ́ aṣẹ́ṣó irun, Kesie Virgin Hair gbà á gẹ́gẹ́ bí aṣojú wọn lọ́dún 2019.Àtòjọ àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópaThe Prince & I (2019)heart of Love (2019)my Sisters Love (2019) Billionaire (2019) goddess (2019) of Love (2019) =The Sacred (2019) (2019)The Return of Ez (2019)Barren Kingdom (2019) of the Orphan (2019) of Royalty (2019) Fid Sind (2019) Family (2019) King's Word (2019) of Evil (2019) Private Part (2019) as Stellapower of Royalty (2019)sun of Love (2019) Prince Prince (2019) of Power (2019) of Do (2018) see (kers (2017) of a Woman (2016) Days to WEWEWE (2016) The Storm (2016) Awọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Sani Musa Abdullahi, tí wọ́n tún mọ̀ sí Sani Danja tàbí Danja tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1973 jẹ́ òsèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, alájọta àti àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù kẹrin ọdún 2018, tí ó jẹ́ Nupesu Nupe, Yahaya Abuka, We láwàní fún gégé bí bí Zali arẹwà.Iṣẹ́ rẹ̀ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ eré ìtàgé Hausa ní ọdún 1999 nínú eré Dalibá.. | wikipedia | yo |
Danja di ilu-mooka ni ọdun 2012 ninu ere Daughter of the River.Awon aṣayan ere ReSani ti kópa ninu ere , ó sì ti gbe ere jade ó sì ti dari eré kannywood àti Nollywood.. | wikipedia | yo |
Aisha Yufu (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá ọdún 1973 ní ìpínlẹ̀ Kano) jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ó ọmọ ènìyàn, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti alabaṣiṣẹpọ ẹgbẹ́ tí ó n polongo fún ìdápadà àwọn ọmọ obìnrin wá (Bring Back Our Girls Movement), èyí tí í ṣe ẹgbẹ́ aláwgbà tí ó ń pe ìjọba sí àkíyèsí lórí í àwọn ọmọbìnrin tí ó lé ní igba láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Isdì ti Chibok ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti àwọn ẹgbẹ́ onílé Boko Haram jí gbé ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Yesufu wà lara awon obinrin ti won n fi eronu han ni ile igbimo asofin ti orile-ede Naijiria, eyi ti o wa ni Abuja, Olu-ilu Naijiria, ni ogbon ojo osu kerin, odun 2014.Yesufu tun wa lara awon ti o lewaju nigba ti awon odo orile-ede Naijiria n pe fun fífòpin si SARS (End SARS), eyi ti o n pe akiyesi si àṣejù ti eya kan ninu ise olopaa orile-ede Naijiria ti won n pe ni Special anti Robery Squ (SARS) n se.. | wikipedia | yo |
Yesufu so wipe oun ko ni fi ija kikede ìfòpin si awon olopaa SARS ni orile-ede Naijiria sile fun awon omo oun.ibẹrẹ aye re Ipinle Kano, nibi ti won bi Yesufu si na a ni won ti to o dagba.. | wikipedia | yo |
Yesufu ni iriri lori i iṣoro ti o wa ninu n ki eniyan jẹ ọmọbinrin ni ayika ti ko fibẹrẹ si imo Eko.. | wikipedia | yo |
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ tí ó sọ, ó wípé “nígbà tí mo wà ní ọmọ ọdún mọ́kànlá, n kò ní àwọn ọmọbìnrin kankan ní ọ̀rẹ́ nítorí pé gbogbo wọn ni wọ́n ti gbé níyàwó, ṣùgbọ́n nítorí mo fẹ́ ní ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ni mo ṣe kúrò ní agbègbè tí kò lajú.” Aisha Yufu tún sọ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn ọmọ tí àwọn ẹlẹ́gbẹ́ òun bí ti fẹ́rẹ̀ tún ma a bí ọmọ nígbàtí òun ṣe ìgbéyàwó ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógún.Ìgbésí ayé rẹ Yesufu àti ọkọ rẹ̀ ti orúkọ rẹ ń jẹ Aliu, ẹni tí ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú rẹ̀ ní ọdún 1966, ni wọ́n bí ọmọ méjì tí orúkọ wọn ń jẹ Amir àti Aliyah.Àwọn ìtọ́kasí àwọn oníṣòwò ará Nàìjíríààwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1973.. | wikipedia | yo |
Abiodun (Abi) Koya (A bí ní ọjọ́ kejìlógún oṣù Kejìlá ọdún 1980) ó jẹ́ ọmọ abínibí ìlú Nàìjíríà, ó jẹ́ olórin aláìlẹ́gbẹ́, akọrin, akéwì, òṣèré, ònkọ̀wé àti onínúrere tí ó tẹ̀dó sí ìlú Amẹ́ríkà.Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n akọrin tín ṣe abínibí ìlú Áfíríkà tó gba ẹ̀kọ́ orin aláìlẹ́gbẹ́.. | wikipedia | yo |
Abiodun Koya tí Kọrin ní White House, níbi àwọn ífínígbè Ààrẹ àti ní àpéjọ National Democratic.. | wikipedia | yo |
A bíi ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ti Nàijíríà, bàbá rẹ̀ gbàá níyànjú lórí orin nípa ṣíṣe àfíhàn orin aláìlẹ́gbẹ́ fún u ní ọmọ ọdún mẹ́ta, Koya nifẹ sí orin nígbàtí ó di ọmọ ọdún mẹ́fà, ó ma ń ta violin, ó sì maa n kọrin aláìlẹ́gbẹ́ ní ilé ijọsin.. | wikipedia | yo |