cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O lo si ile-iwe giga ti Queen ki o to di wipe o lo si kọlẹji ti imo-ẹrọ ti o wa ni Yaba (Yaba College of Technology), nibi ti o ti je wipe oun nikan soso ni obinrin ni aarin awon akeko ni odun 1946..
wikipedia
yo
Adetoun ni obinrin akoko ti o koko keko gboye mejidinlogota jade ni ile-eko yi ni odun 1948..
wikipedia
yo
O lo si ile-eko giga Yunifasiti iluIbadan ki o to di wipe o ni anfaani si Eko ofe lo si ile-eko giga Newn ti ti ipinle iluCambridge ni orile-ede Geesi lati lo ko eko lori Geography..
wikipedia
yo
O gba oye akoko ti Yunifasiti (Bachesáwọn of Art degree) ni odun 1952 ati oye eleekeji (Masters of Art degree) ni odun 1956 ni sise n tele ni ile-eko giga yi, nibi ti o ti je wipe oun ni obinrin akoko lati orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O gba oye giga ti Yunifasiti eleekeji miran lori imo nipa Idun pamo si ka lati ile-eko giga ti Simmons, ti o wa ni Massachusetts, USA ni odun 1962.Adetoun ni o da ile ikawe ti Abadínà media Resources Centre ti o wa ni ile-eko giga Yunifasiti ilu Ibadan sile ni odun 1973..
wikipedia
yo
O di ojogbon ni ile-eko giga Yunifasiti iluIbadan..
wikipedia
yo
Ni Yunifasiti ilu Ibadan yi ni won ti yan an gege bi i oga agba ti eka eko laarin odun 1977 si odun 1979..
wikipedia
yo
Òun ni ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí wọ́n má a kọ́kọ́ yàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì kankan ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti sise gege bi i onimoran fun orisirisi ile ise..
wikipedia
yo
Lara won ni ile ifowopamo ti agbaye (World Bank); International Federation of Library Associations and institutions (If); UNESCO; International Association of School LIrianBERship (Iún); International Federation of Documentation (dFID) ati British Council.Àwọn ọlá àti iyìn tí wọ́n bú fún Adetoun àwọn ọlá àti iyìn oríṣiríṣi ní Adetoun Ogunseye ti gbà..
wikipedia
yo
Doctor of Letters (D.litt) ti Yinifasiti ilu Maiduguri.
wikipedia
yo
Ní ọdún 1985, ó gba ìyìn tí Nigeria Academic of Education ní ọdún 1985, ó gba Decade of Women Certificate of Merit for Outstanding Achievement.
wikipedia
yo
Ni ọdun 1982, o gba Fellow, Nigerian Library Association.
wikipedia
yo
Ni ọdun 1980, o gba Fulbright Fellowship for Senior African Scholars.
wikipedia
yo
Ní ọdún 1979, ó gba àmì ẹ̀yẹ ti Simmons College International Alumnus.
wikipedia
yo
Ni ọdun 1961, o gba Ford International Fellow.Ile Eko giga Yunifásítì Ìbàdàn tún sọ gbọngan ibugbe kan ti àwọn ọmọ ile-ẹkọ n gbe ni orukọ rẹ ni akoko ti ojogbon Abel Idowu Olayinka n ṣe iṣakoso ile-ẹkọ giga Yunifasiti yi.Awon itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1926awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Saidat Adegoke ti won bi lọjọ kẹrinlelogun osu Kesan-an Odun 1985 (24 September 1985) ni Ilu Ìlọrin, Ipinle Kwara , LÓRÍLẸ̀ ede Naijiria je agbaboolu-afẹsẹgba obinrin.Iṣẹ re bi agbabọọlu-afẹsẹgba obinrin o bẹrẹ si ni gba boolu jẹun fun Ikọ̀ Ẹgbẹ Agba-afẹsẹgba ti Remo Queens ni Naijiria..
wikipedia
yo
Leyin naa, o dara po mo iko egbe agbaboolu-afẹsẹgba ACF Trento ni orile ede Italy..
wikipedia
yo
O gba bọọlu mẹta sáwọn fun ikọ rẹ ninu ifẹsẹwọnsẹ merindinlogun..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó dara pọ̀ mọ́ ìkọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ACF Milan lóṣù kẹjọ ọdún 2008..
wikipedia
yo
In Milan she developed and by Summer 2011, Scored 19 goals in 52 Games..
wikipedia
yo
At the beginning of the Season 2011/2012 she changed to FCf Como 2000.Iṣẹ rẹ loke-okun lati ọdun 2010, o jẹ ọkan lara awon iko agbabọọlu-afẹsẹgba obinrin ti orile ede Naijiria.Awon itọkasi ita awon Ọjọ́ìbí ni 1985awon eniyan Alaayẹ̀wò's Association football Ọ̀DỌ́KÙNRIN Women's footba women's International footba Kanlssa.C..
wikipedia
yo
Milan women FaraorsNigerian exPatriate Women's footballersNigerian exPatriate Sportspeople in italxxPatteriate Women's footballers in Italyàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Salma Phillips jẹ́ atọ́kùn ètò tẹlifísàn, Òǹkọ̀wé àti Olóòtú ètò láti ìlà-oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn ètò lóri àwọn ìkànnì tẹlifíṣàn lápá ila-oorun Nàìjíríà.She is popularly known as the Face of Northern Television.Ó kàwé gbábo ẹ̀rí Dipọlọ láti University of Jos, ní Nàìjíríà àti ìwé ẹ̀rí BSc
wikipedia
yo
Ninu imo ofin lati Rivers State University of Science and Technology, ni Port Harcourt..
wikipedia
yo
Àlá àyè rẹ ni láti jẹ́ oníròyìn fún CNN.Ìbẹ̀rẹ̀ ReSalma jẹ́ àmúlùmálà ẹ̀yàFúlàní àti Cvbárì láti apá àríwá Nàìjíríà, ó sìn fẹ́ràn orin Takasúfèé.Iṣẹ́ rẹ̀Salma kàwé gbàwé ẹ̀rí dìlọ̀pọlọ láti University of Jos, ní Nàìjíríà àti ìwé ẹ̀rí BSc
wikipedia
yo
Salma àti gbajúgbajà olórin ọmọ Nàìjíríà, àṣà, dìjọ lọ sí ilé-ìwé kọ́lẹ́ẹ̀jì kan náà..
wikipedia
yo
Lọ́jọ́ keje oṣù kejì ọdún 2016,ó bẹ̀rẹ̀ ètò orí tẹlifísàn tí ó pé ní Salma Show, ètò tó dá lórí ọ̀rọ̀ tó ń lọ láwùjọ..
wikipedia
yo
Sarah Michael tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún Ọdún 1999 (22 July 1990) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je agbaboolu-Ife.O je omo egbe iko agbaboolu-afẹsẹgba obinrin ti Naijiria, o sin wa lara awon iko obinrin agbaboolu-afẹsẹgba ti idije boolu-afẹsẹgba Olympics lodun ati idije 2011 World Cup.Awon itọkasi ita awon Ọjọ́ìbí awon Ọjọ́ìbí ni 1990awon eniyan ominira's foot's footte·te women's footba Sweden in Sweden Fujite footba foot, Exxte Sportste Inru Sweden at the 2008 Summer Olympicso footso foot of Nigeria FIFA FIFA's World Cup Marie In Orers Dakoko In Domi Inoríṣi Inoríṣi I Fot (Women 2020 If (Women Women Women' Women Women's International foot's Association football oniseṣàwọn itọkasis
wikipedia
yo
Adunni Bankole (Oṣù Kẹta, ọdún 1959 – ọjọ́ kẹta oṣù kini ọdún 2015) jẹ́ ólùdarí àwùjọ ní nàìjíríà àti obìnrin oníṣòwò..
wikipedia
yo
ó jẹ́ yéye mókun ti ìjọba Òwu, ìlú kan ní Abẹ́òkúta, Olú-Ìlú ti ìpínlẹ̀ Ògùn, gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà .Ìgbésí ayé a bí ní oṣù Kẹ́ta ọdún 1959 ní Òwu ti Abẹ́òkúta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú olóṣèlú ìjọba olómìniraa kejì, Olóyè Àlàní Bankole tí ó jẹ́ Bàbá fún agbọ̀rọ̀sọ tẹ́lẹ̀ ti ilẹ̀ àwọn aṣojú, Ọlọ́lá Dimeji Bankole .ikú ó kú nípa ìkọlù ọ̀kan ní ọjọ́ kẹta oṣù kíní ọdún 2015 lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ́ ọkàn..
wikipedia
yo
ìròyìn wípé ó kú ní wákàtí díẹ̀ ṣáájú ayẹyẹ ìgbéyàwó ti ọmọbìrin rẹ̀.Wo eleyĩ nã Dimeji Bankoleàwọn ìtọ́kasí àwọn ọjọ́aláìsí ní 2015àwọn Ọjọ́ìbí ní 1959àwọn ọmọ YORÙàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Abiola odeJide je ojogbon-agba ninu imo ise-ona ede ati Litireso lati Yunifasiti Ibadan, (University of Ibadan)..
wikipedia
yo
Ó ti kọ́kọ́ jẹ́ igbákejì Ọ̀gá Yunifásítì Lábala ètò ẹ̀kọ́ ní University of Ìbàdàn, òun sìn ní obìnrin àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ dé irú ipò bẹ́ẹ̀ lọ́mọ ọdún méjìdínlọ́gọ́ta.Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀abí Aobají kàwé gboyè digírì Àkókò pẹ̀lú èsì ìdánwò tó dára nínú ìmọ̀ èdè Òyìnbó ní University of Ìbàdàn lọ́dún 1968..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó lọ sí University of Leeds lókè okun láti kàwé gboyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ tí Linùnọmọbìnrin àti èdè òyìnbó pẹ̀lú èsì tó dára jù lọ lọ́dún..
wikipedia
yo
O gboye omowe lodun 1986,o sin di ojogbon sise lodun 1991 ni University of Ibadan.Awon ipo asoju to dìmúodeJide ni obinrin akoko ti o k9ko je igbakeji oga Yunifasiti ni University of Ibadan..
wikipedia
yo
A!Ṣáájú àkókò náà, ó ti kọ́kọ́ di oríṣiríṣi ipò mú, lára àwọn ipò tó jẹ́ ni; olùdarí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Òkèèrè..
wikipedia
yo
Ó sinmi lẹ́nu iṣẹ́ ní Ìbàdàn lóròyìn kọkànlá ọdún 2011.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oloye Abibátù Mọ́gàjí, MFR, OON tí wọ́n bí ní ọdún 1917, tí ó sì kú ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2013 (October 1917-June 2013) jẹ́ =parakoyi onílà ọmọ Nàìjíríà àti Iyalọlọ́jà yányán gbogbo Nàìjíríà.Ìgbà Ewén kò bí Abibá Mọ́gàjí lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́ Oṣù Kẹwàá Ọdún 1916 ní Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríàẹbí rẹ̀Olóyè Abibá Mọ́gàjí ní Ìyá Olórí Ẹgbẹ́ Òṣèlú All Progressives Congress tí ó tún jẹ́ gómìnà àná Ìpínlẹ̀ Èkó, Olóyè Asiwaju Bola Ahmed Tinubu..
wikipedia
yo
Ọmọ Tinúbú, Fọláṣadé Tinúbú-ọjọ́, ló joyè ìyálọ́jà lẹ́yìn ikú Mọ́gàjí.Iṣẹ́ rẹ̀kí ó tó jẹ́ ìyálọ́jà àwọn ẹgbẹ́ àwọn ontàjà àwọn obìnrin àti ọkùnrin, abítù jẹ́ olórí onígboyà àwọn ọlọ́jà ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ipò rẹ̀, ó joyè alágbára Alimotu pẹ̀lẹ́wúrà.Nípa akitiyan rẹ̀ láàárín àwọn ọlọ́jà, ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà fi oyè orílẹ̀ èdè dá a lọ́lá..
wikipedia
yo
.Bẹ́ẹ̀ náà, wọ́n fi oyè ọ̀mọ̀wé dá a lọ́lá ní Ahmadu Bello University and the University of Lagos.Ikú rẹ̀iyalọ́jà Mọ́gàjí ku lọ́mọdún mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún ní Sátidé, lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹfà ọdún 2013 nílé rẹ̀ tó wà ní Ikeja, olú-ìlú ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Wọ́n sin in sí itẹ́ òkú ti Ikoyi Ìdádited and Gardens ni Ekoàwọn amin ẹyẹOrder of the Federal rẹpúd of the nígèélẹ itọkasi..
wikipedia
yo
jẹ́ ọmọ ọdún márùnlélọ́gbọ̀n òṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn sí ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà láti ṣojú ìpínlẹ̀ Minnesota..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ àlùfáà ìjọ Episcopal ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó fi Amẹ́ríkà ṣe ibùgbé..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ àfọwọ́ṣàánú tí ó kọ́ ibùgbé fún àwọn ọmọ aláìlóbìí..
wikipedia
yo
Esther ni yóò sojú agbègbè District 59b ní ìpínlẹ̀ Minnesota nílé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀agbègbè kan ní St..
wikipedia
yo
Paul nílùú Brainerd lágbègbè Farìbát lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ní àwọn òbí rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ ọmọ Nàìjíríà bíi Ṣiwon..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin ní Harvard Law School kí ó tó padà sí òdò àwọn òbí rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Minnesota dún 2017..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òṣèlú, (Political Science) ní The George Washington University ní Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè dìgírì kejì ní University of Pennsylvania kí ó tó dára pọ̀ mọ́ Òṣèlú.Iṣẹ́ rẹ̀Lọ́dún 2019, Esther gba ojú-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi àní ètò tó jù lọ ní Ìpínlẹ̀ Minnesota fún akíkanjú àti akitiyan rẹ̀ nínu iṣẹ́ àgbẹ̀mọ́, pàápàá jù lọ nípa ìjí fún ètò àwọn ayalegbe..
wikipedia
yo
Kí ó tó di àsìkò yìí, ó ti ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ ti Amẹ́ríkà, Ú.S..
wikipedia
yo
Ti orukọ àbísọ rẹ̀ gan jẹ́ Antiààmì Oyedúpé Payne, tí wọ́n bí lọ́dún 1995 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ọmọ Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O maa n gba boolu gege agbayosáwọn fun iko agbaboolu-afẹsẹgba obinrin Sevilla lorilẹ-ede Italy.Ìgbésí-ayé rẹwọn bi Toñi Payne ni Birmingham, Alabama, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà si idile awon omo Naijiria to fi Amẹrika se ibugbe, ti won sin to o ni United States.Payne gba boolu fun Ikọ̀ Agba-afẹsẹgba Ojewewe Obìnrin Amẹ́ríkà ti ojo ori won ko ju mẹ́tàlélógún lọ lodun 2012..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2016 sí 2018, ó gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ti Ajax..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2018, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin SeVilla..
wikipedia
yo
lọ́dún 2019 fi èròǹgbà rẹ han láti dára pọ̀ mọ́ ìkọ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ti Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
{{Infobox person| name | Sala = Àbí gbangba Sanusi | Image | Image – = 180p| Al | Nigi | Caption | Birth date | Birth Place Place – Nàìjíríà| Deathdate date =| Deathplace Place =| Body discovered = Cauka Death Gu =| Ohunrin Place =| Mélòóbe Place=| Nationality = Ọmọ Nàìjíríà | Ethnicity = Yorùbá| Citizenship =| Other names = ↑ known for *_
wikipedia
yo
Ó kàwé lórílẹ̀ èdè England ní Leeds University.Àbíṣẹ́ ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn, tí ó sìn ṣíṣe ìbánimójútó ìkànnì ayélujára fún àwọn òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
Iwe itan aroso Kemi's Journal ti o ko lodun 2005 ni iwe apileko re akoko, leyin naa lo ko Zack's story of Life, Love and Everythingati God has daughters too.iwe-itan-aroso ti o ko leyin ti akole re n je Eyo, ti ile ise atewe, wordalive Publishers te jade ni won yan fun Àmín-èye ti Commonwealth Writers' Prizelodun 2010.Awon iwe rèéyo (2009)Kemi's Journal (2005)God has daughters too' (2006)Zack story of Life, Love and Everything (2006)àwọn itọkasis)àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1957,(26 July 1957) jẹ́ ọ̀pọ̀ sí Ààrẹ-àná ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹni tí ó tún jẹ́ gómìnà-àná ìpínlẹ̀ Kat, Umaru Musa Yar'Adua..
wikipedia
yo
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2007 títí ọkọ rẹ̀, Ààrẹ-àná, Yar'Adua fi ta tẹrú nípàá lọ́jọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 2010.Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀wọ́n bí turai Yar'Adua ní ìpínlẹ̀ Katn lápá àríwá Nàìjíríà lóṣù keje ọdún 1957..
wikipedia
yo
Ó kàwé ní Government girls Secondary school ní kànkiya nígbà ewé rẹ̀.Ira Yar'Adua kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ìpára Primary School ní ìṣàkóso, tí ó sìn kẹ́kọ̀ọ́ girama ní ní government Secondary School ní kankia, ní ìpínlẹ̀ Kat bákan náà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó kàwé ní ìṣàkóso College of Arts, Science and Technology ní Zaria, ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, níbi tí wọ́n ti sọ pé òun ni akẹ́kọ̀ọ́ tó mọ̀wé jù nígbà náà lọ́dún 1980..
wikipedia
yo
In 1983, Yar'Adua received a Bachelor's degree in language from Ahmadu Bello University.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ti àpèjá orukọ àbísọ rẹ̀ n jẹ́ Alon Abisola múraCate Àjọkẹ́ Ọ̀làjúwọn, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣu Keje Ọdún 1988 jẹ́ akọni àti agbábọ́ọ̀lù-àjò ọmọ orílẹ̀ ède Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọbinrin gbajumọ agbabọọlu-Àjùsáwọn, Hakeem ìfọwọn..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ìtumọ̀ orúkọ rẹ̀, Abisola Ọ̀làjúwọn, ó jẹ́ ọmọ Atà-dìde, ọmọ tí wọ́n bí sinu ọlá, tí ọlá náà ju àwọn ju àwọn ọ̀tá lọ.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù-ọnwọ́n ilé ẹ̀kọ́ gíga àti Kọ́lẹ́ẹ̀jìwọn bí ọ̀làjúwọ́n sí Houston, ní ìpínlẹ̀ Texas lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó wà nínú ikọ̀ tí wọ́n ń gbá bọ́ọ̀lù-ọ́nòrùn fún ilé-ìwé gíga California àti ní, ó sin rànwọ́nlọ́wọ́ láti gba àmìn-ẹ̀yẹ mẹ́ta léraléra nínú ìdíje apá ìwọ̀-oòrùn Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
ọ̀làjúwọ́n gbamin-ẹyẹ ti McDonald's All-American lọ́dún 2006, ó tún wà lára àwọn tí wọ́n gba Àmín-ẹ̀yẹ tó pọ̀ jùlọ tí wọ́n jáde ní ilé-ìwé gíga..
wikipedia
yo
O gba bọọlu-edeṣàwọn fun University of Oklahoma, ni asiko yii Nancy Lieberman, asayẹ̀wò bọ́ọ̀lù-Àjùs ti ilé-iṣẹ́ ESPN sọ wípé, díUK Ọ̀làjúwon sí Ikọ̀ rẹ̀ fún ìdíje ti ọdún 2006 sí 2007 yóò mú kí wọ́n ṣe àìyọrí fún ìdíje NCAA.Lọ́dún 2010, ó kàwé gboyè digírì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ ìròyìn láti OK University.Àṣàyàn iṣẹ́ rẹ̀ ni OK Universitysoursé rẹ̀ nínú iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àjò ẹgbẹ́ Sky Yan ọ̀làjúwọn sí ipò méjìdínlọ́gbọ̀n nínú àwọn tó mọ́ bọ́ọ̀lù-àjò gbà jùlọ ní àgbáyé ní ìdíje LỌ́DÚN 2010..
wikipedia
yo
lẹ́yìn èyí, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-ọnwọ́n ní orílẹ̀ èdè Hungary, seat-lámì-ved Gllow, àti ti Romania.Ní 2011 ọ̀làjúwọ́n padà sí WNBA, tí ó sin tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn fún ikọ̀ Tulsa Shock, ibẹ̀ ló ti díje fún sáà ìdíje ọdún 2011 Season.Nígbà ìsinmi, ó gbá bọ́ọ̀lù-ánsẹ̀ fún Hapoel risHon Lezion (Israel), Z_*ZUn Zusist (Croatia), BC Caroòwú Braine (Belgium)..
wikipedia
yo
Leyin eyi, o gba boolu fun Esseley Ourin (Brazil), ati Heakoko Chegen (China (China).Won gba isinmi ole gbigba-eyi ni iko orile ede Italy, caja Rural Zani itọkasi.àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Fatima Binta Bello ti o je olukọ, Kọnaroyin nigba kan, ti o sin je igbakeji olopaa, Deputy Minaya àtìmọ́lé, ile igbimo asoju-sofin, Nigerian House of Representatives tele..
wikipedia
yo
Tí ó ń ṣẹ ẹkùn ìdìbò Kaltungo/NGO ti ìpínlẹ̀ Gombe tẹ́lẹ̀, je gbajumo oselu-binrin omo Naijiria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP, òun nìkan ni obìnrin tí ó wà nínú àwọn ìgbìmọ̀ àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó wà ní ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin Nàìjíríà lásìkò rẹ̀.Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀wọ́n bí Binta ní ìlú was born in Igbúzo ní ìpínlẹ̀ Delta lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ajagun-fẹ̀yìntì ni baba rẹ̀..
wikipedia
yo
She moved all around the country before finally returning to her native Gombe state.Ó kàwé gboye ìwé ẹ̀ka onípele méjì (Teachers Grade II Certificate) lati w.2.C jojoga, ní ìpínlẹ̀ Gombe lodun 1988, àti ìwé Erija Dipọlọ ninu ìmọ̀ ẹto òàwùjọ (Public Administration) ní University of Jos lodun 1995, * ati iwe eri b.
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ ètò láti University of Maiduguri lọ́dún 2010.IṢẸ́ yàn Binta gẹ́gẹ́ bí Kọmíkòmí fún ètò obìnrin ní Ìpínlẹ̀ (SAN LỌ́DÚN 2007 sí 2010 ..
wikipedia
yo
O dije dupo fun ile Igbimọ Aṣoju-sofin ti Ẹkùn idibo ijọba apapọ ti Kaltungo/shoNGO labẹ ẹgbẹ oṣelu People's Democratic Party, ti o sin wọle..
wikipedia
yo
Awon akegbe re obinrin ti won tun wole idibo nigba naa labe PDP ni Nnenna elendu-24th, sọdáguno Festus Omoni, Nkírúka Chidubem Onyejecasal, Rita Orji, Evelyn omavovoan ọ̀bọ̀rọ́, Beni butmaklar LangTang, OmoSede Icedion Gabriella, Stella Obiageli ngwu ati EUcharia Okwunna.lodun 2019, o tun dije, sugbon o padanu ṣowó akẹgbẹ́ ti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, Amos Bulus.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adé Hassan Adétola Kunle-Hassan, ti a mọ si Ade Hassan, mbe, (ọjọ́ ìbí April 1984) ó jẹ́ oníṣòwò obìnrin láti ìlú òyìnbó tí ó dá Nise Skin sílẹ̀ ní 2004.Ìbẹ̀rẹ̀ àyè kòpò bí Hassan ní Oṣù Igbe ní ọdún 1984..
wikipedia
yo
Ó lọ ilé ìwé gíga ní Duke University ní ilé ọba níbití ó ti kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti ẹ̀kọ́nomisí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè dìgírì ní ilé ìwé Oriental and African Studies ní ìlú àtẹ̀oretọ́-ẹ̀kọ́ rẹ̀ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Èkó rẹ̀ wáyé ní Private-Ebanijẹ́business..
wikipedia
yo
Sugbon o akoko die nibe lati lo fun eko gígé ati rírán fun odun kan. O da nuBian skin sile, ti o n se àwọ̀tẹ́lẹ̀ ni dudu tones fun awon obinrin, 2014 leyin ti o ti le ra aṣọ fun ara re ni orisirisi àwọ. Ni 2014, a so o di onisowo Oge ti odun naar ni The Great British Entrepreneur Awards. Ni osu ọ̀wàrà odun 2015, a yan ade's Brand, nuBian skin, fun HOSiry Brand ti odun naa ni UK lingerie awards[10] O si jawe olubori UK's favourite British Desiner ti odun naa. A yan-an gegebi egbe egbe ti order of the British Empire ni 2017 Queen's birthday Hongiurs for Services to Fashion.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Amina Olukiniza Bello, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejì Oṣù Kẹrin ọdún (2 April 1978) jẹ́ Agbẹ́jọ́, àfọwọ́ṣàánú àti ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ kogi, Yahaya Bello, kogi State Governor..
wikipedia
yo
Òun ni alága àti olùdásílẹ̀ FairPlus International, Fkòb Foundation, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ Parakoyi oníṣòwò..
wikipedia
yo
Amina kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin láti Obafemi Awolowo University ní Ile-Ife ní ìpínlẹ̀ Oyo ní Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adama Ndiaye, tabi Adama Amanda Ndiaye, ti gbogbo eniyan mo si Adama Paris (ti o tun je orukọ ile-iṣẹ rẹ) , ni a bi ilu Kinshasa..
wikipedia
yo
Awon aṣọ ti o n ran ni o ma n ko wole lati orile-ede Morocco ti a si le ri awon aṣọ re ra ni awon orile-ede agbaye gbogbo bi Parague, Bahia, Paris, Montreal,London ,New York ati bee bee lo.igbesi aye Rendi ni won bi ni ilu Kinshasa, ti won si to da ni Europe, nibi ti awon obi re ti je asoju ijoba ilu ijoba ilu..
wikipedia
yo
Ó fi iṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ nílé ìfowó-pamọ́ ní Europe láti lọ kọ́ iṣẹ́ aṣọ rírán ní ìlú abí rẹ̀..
wikipedia
yo
Nínú ìgbàgbọ́ rẹ̀, ó mọ̀ wípé ilẹ̀ Áfíríkà ní àwọn àṣà ìránṣo tó ṣe pàtàkì, àmọ́ tí wọn kò gbajúmọ̀ ní àwọn orílẹ̀ àgbáyé tó kù..
wikipedia
yo
Kí ó tó rí owó dá ilé-iṣẹ́ aṣọ rírán rẹ̀ sílẹ̀ sọ́rọ̀ díẹ̀ pẹ̀lú.áyédi da ìdíje fashion week sílẹ̀ ní ìlú Dakar láti lè fẹ́ iṣẹ́ ọ̀nà ìránṣọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ síwájú sí..
wikipedia
yo
Nígbà tí yóó fi di ọdún 2012, tí ìdíje náà pé ọdún wáwá gbá, àwọn oníṣẹ́ ọ̀nà ààtín ọgbọ̀n ní wọn ti dara pọ̀ mọ́ Ndiayé ní ilẹ̀ Áfíríkà àti Asia, pẹ̀lú àwọn olùkópa míràn KÁRÍ ayé..
wikipedia
yo
Ilé iṣẹ́ rẹ̀ sì ti ń ṣe ìṣúná tí ó tó Cfa 80 Milion ( tí ó jẹ́ US$150,000)..
wikipedia
yo
Bakan naa ni o ti gbe idije yi de Prague, Czech Republic, ati Bahia, Brazil.Awon itọka si..
wikipedia
yo
Jayéọla Àdùkẹ́ Alakija tí wọ́n bí Lóṣù Kẹta Ọdún 1921,tí ó sìn kú Lóṣù Kẹta Ọdún 2016 (March 1921 – March 2016) jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká ọmọ Nàìjíríà tí ó fìgbà kan jẹ́ òṣìṣẹ́ alamojuto, amo àti aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè Sweden tẹ́lẹ̀ láti ọdún 1984 sí 1987..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ló fìgbà jẹ́ Ààrẹ àwọn ẹgbẹ́ amòfin-bìnrin, International Federation of Women Lawyers.Ìgbésí-ayé rẹ̀wọ́n bí Àdùkẹ́ sí ìdílé Adeyẹ Alakija, òun ni àbígbẹ̀yìn àti ọmọbìnrin kanṣoṣo tí baba rẹ̀ bí..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Claxton House School, ní Marina, ní ẹ̀kọ́ kí ó tó mórí lé Orílẹ̀ Èdè Wales lọ́dún 1930 fún ẹ̀kọ́ sí i níbi tí ó ti parí ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní Penrhos College, lápá Àríwá Wales..
wikipedia
yo