cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O si wa láàarín awọn ti o ṣe ofin fun awọn alabo ara ni Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù kìíní ọdún 2017, ó sì ṣe pẹ̀lú Benola cerebral palsy inititheun.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kejì Ọdún 2018, ó gbé ètò kan kalẹ̀ tí ó fi ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọ tí ó bá ní àrùn cerebral palsy.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
wunmi Mosaku (bíi ní ọdún 1986) jẹ́ òṣèré àti olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun ipa Joy ti o ko ninu ere Moses Jones (2009) ati Holly Lawson ninu ere Vera(2011).. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì ẹ̀yẹ Best Supporting Actress láti ọ̀dọ BAFTA TV Award fún ipa Gloria Taylor tí ó kó nínú eré Damilola, Our Loved Boy ní ọdún 2016.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó kópa nínu ipa karun-un ti fíìmù Luther.ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí Mosakú sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà amọ̀ wọ́n gbé lọ sí ìlú Manchester ní orílẹ̀ èdè England.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Trinity Church of England High School àti XAveBER sixth Fordi College.Iṣẹ́ Mosakú gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Royal Academy of Dramatic Art ní ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́kọ́ yàn lórí eré orí ìtàgé nínú eré The Great Theatre of the World èyí tí Pedro Calderon gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà, ó ti kópa nínu eré Rough Crossing èyí èyí tí Rupert Goold ṣe adarí fún.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, ó kópa nínu eré Ìsìndì Katrina.Ó farahan nínu ìwé ìròyìn ní ojú ìwé àkọ́kọ́ ti screen International ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2009 gẹ́gẹ́ bi ikan lára àwọn gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè UK.Ní ọdún 2010, ó kó ipa Úru nínu eré I Am Slave, èyí ló sì jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré binrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ Birmingham Black Film Festival, Culture diversity Awards àti screen Nation Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó kó ipa Quentíná nínu eré Capital èyí tí BBC gbé kalẹ̀.àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Charity Chinonso èké, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Chacha èké fààní, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlógun Oṣù Keje Ọdún 1987 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ Ìpínlẹ̀ Ebonyi lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká nígbà tó kópa nínú sinimá kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ The End Is Near lọ́dún 2012 .Ìgbésí ayé rẹ̀ ni Ewe, Ìkẹ́kọ̀ọ́ àti Iṣẹ́ Láí bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ni Èṣùt Nursery & Primary School ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi , lẹ́yìn máa o kàwé ní Our Lord Shepherd International School ní Ẹnúgi.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè BSc ní ẹbọnyí State University nínú ìmọ̀ ìṣirò-Owo. àwọn àyàn sinimá Siniè rẹ̀ rẹ̀ His nearder In Chief In of Thunder Herinbeach 24gi of PAina Cryina for Justice of the Sunbloody Carnivallo for the PrincEmir of Life Life Pain of contract of Sorrowsecret Dókítàs Dókítàs Dókítàru Promise of Tears Love Angel Angel My Love Love Rising sun Sweet Loeseese Eroko Missionvgen Gvborn Wsha’’me to Bad People Stars of the Godslélẹ̀ Hear ní Blood of Destiny Sound of Ikọ̀swewe of SorrowBasket of SorrowFestival of Sorrowkamsi the Freedom Fidu Fiami Riches at Warṣàtúnṣesing The Battle Line line with Blood with Blood Who took my husband alive of Love Only Rometan Uroko First Lady Beau Beau The altar Campus Campus's Redage’’my Last Blood’’àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Yvonne Anuli Orji (Bii ni ojo keji osu kejila odun 1983) je osere ni orile ede Naijiria ati Amerika.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínu eré Insecure ní ọdún 2016, èyí tí ó jẹ́ kí wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ti Primetime Emmy Award àti NAACP Image Awards.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bi Orji ní ọjọ́ kejì Oṣù kejìlá Ọdún 1983 sí ìlú Port Harcourt ní Ìpínlẹ̀ Rivers ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó sì dàgbà sí ìlú Lauren ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti George Washington University níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Liberal Arts.Ní ọdún 2009, ó lọ sí ìlú New York City láti ṣe iṣẹ́ aláwàdà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó kó ipa Molly nínu eré Insecure.Ní ọdún 2008, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Population Services International fún Oṣù mẹ́fà lórílẹ̀ èdè Liberia.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bi Outstanding Supporting Actress in a Comedy series láti ọ̀dọ Primetime Emmy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré Insecure.àṣàyàn àwọn eré tí ó ti ṣeàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Yetunde Barnabas jẹ oṣere, Rori ati olugbe jade ere fiimu agbelewo ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun igba orókè ti o gbe ninu idije obinrin ti o rewa julọ ni Ipinle Abuja ni ọdun 2017 ati Miss Tourism ni ọdun 2019.. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa Miss pẹ́pẹ́íyẹ nínú eré pápá Ajasco and company.Ìbẹ̀rẹ̀ ìsìn ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí ○ sí ìpínlẹ̀ Abuja, àmọ́ ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ ̀èèè ní orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Kings of Kings Secondary School kí ó tó wa tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Seris Ọlọ́pọlọ Production and Royal Art Academy.Iṣẹ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Rch́ nígbà ó lọ fún ìdíje Miss Olokun ní ọdún 2013, òun sì ní ó gbé ìgbà ẹpa.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu oríṣìíríṣìí ìdíje fún àwọn arẹwà obìnrin bíi Miss Live Your Dream ní ọdún 2014 àti ìdíje tíì obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Abuja ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Igba orókè tí ó kó nínú ìdíje ti Abuja yìí ni ó jẹ́ kí ó gbajúmọ̀ gidi gan-an, èyí sì ló jẹ́ kí ilé iṣẹ́ Multichoice fi ṣe AmBase wọn.Ó kó ipa Miss pẹ́pẹ́íyẹ nínu eré Pápá Ajasco, ó sì ti farahan nínu àwọn eré bíi Erin Folami, Dagogo, ọmọ ìyá Osun àti ẹlẹ́gbẹ́nla.Ẹ̀bùn ní ọdún 2019, Wọ́n yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Most Promising Actress of the Year láti ọ̀dọ Nigerian Achiver's Award, Model of the Year láti Odò SAMRE Awards àti Beauty Queen of the Year láti ọ̀dọ Africa Choice Awards.. | wikipedia | yo |
Ni osu kejo odun 2019, won yan ohun ati awon modeli miran lati ile Adulawo lati se asoju fun eto Etomi eyi ti British Broadcasting Corporation gbe kale.aṣayan awon ere ti o ti se 2017 - date - papa Ajasco & company2017 - Agbaya marunmarun - Èdè meji2018 - Lisa - Queen Mi2018 - Ọmọ Ìyá Osun2019 - Ọkà Ori Oroko - ìmùlẹ̀ Aje2019 - lori Titi2019 - Olóde 2019– Omijé Aroko Afọ́jú- knockout Waila- Daroko -2019 Aiye2019 - ẹlẹ́gbẹ́ Oninla- Báyọ̀ Soba- Erin Folamiàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma ṣe iṣẹ́ mẹ́ko ni Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile Lady Mechanic Initiative tí ó gbé kalẹ̀ láti ran àwọn obìnrin tí ó lè tó ara wọn.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, wọ́n ṣe eré nípa ìtàn ayé rẹ̀, eré náà sì gba àmì ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ New York Film Festival.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì ẹ̀yẹ Inspirational woman of the Year láti ọ̀dọ̀ gómìnà tẹ́lẹ̀, Akinwunmi Ambode.. | wikipedia | yo |
Ijoba apapo ti Naijiria si ti fun ni ami eye.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Fọláṣadé noimat Okoya (Bii ní ojo kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, osu kerin odun 1977) je alakóso fun ile-ise Eleganza Group eyi ti oko re gbe kale.ibẹrẹ pepe aye ati eko re won bi Folashade ni ojo kẹẹdọgbọn, osu kerin odun 1977 si idile Alhaji tajú ati alhaja nimosat adeléye si ilu Eko.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ mùsùlùmí, ó sì wá láti Ìjẹ̀bú Òde ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
O gboye ninu imo ifowopamo jade ile eko Lagos State Polytechnic.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ siwaju sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Lagos níbi tí ó ti gboyè ninu ìmọ̀ sociology.Ìgbésí ayé rẹ̀ Folashade fẹ́ Razaq Okoya nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mọ́kànlélógún, ní àkókò tí ọkọ rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́ta.. | wikipedia | yo |
Folashade ni oludasile idije Folashade Okoya Kids Cup.Ni ojo ketalelogun, osu kejo odun 2014, ile eko giga ti European American University fun ni iwe eri ninu imo Business Management and Corporate Leadership.. | wikipedia | yo |
O gba ami jìyà executive woman of the year Award ni osu kejo odun 2018.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Sharon IkeAzor (Bii ni ojo kejidinlọgbọn, osu kejo ọdun 1961) je agbejoro ati oloselu ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Òun ni akọ̀wé tẹ́lẹ̀ fún Pension Transitional BenÌbéèrèment Directorate.. | wikipedia | yo |
Ni osu kejo odun 2019, o di Minisita lori Oro Ayika ni orile ede Naijiria.ibẹrẹ pepe aye ati Eko rẹ Sharon bẹrẹ eto Eko ile iwe alakọbẹrẹ ni St Mary's Conwàá School ni Ilu Eko.. | wikipedia | yo |
Lehinna, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queen of the Rosary College ní ìlú Onitsha.. | wikipedia | yo |
O pari eko giga re ni Yunifasiti Ahmadu Bello ni odun 1981, o si gboye ninu imo ofin lati Yunifasiti ti Benin ni odun 1984.Iṣẹ IkeAzor ti ṣe onimoran ofin fun awon ile ifowopamo Nigeria Merchant Bank, Npàdéìyànce middenstandbank ati Miss Merchant Bank.. | wikipedia | yo |
Ó sì ṣe pẹ̀lú Shell Petroleum gẹ́gẹ́ bi agbẹjọ́rò ilé iṣẹ́ náà ṣáájú ìṣètò ilé iṣẹ́ òfin tirẹ̀ ni ọdún 1994.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1999, o jẹ akọwe ofin ati alakoso iṣẹ akanṣe fun fluor Daniel Nigeria Ltd.. | wikipedia | yo |
IkeAzor di igbá keji fun idagbasoke iṣowo ati awọn ibatan ijọba fun Ile Iṣẹ Onimọ̀ràn ti United States, Good Works International (Gwi) lati ọdun 2003 titi di ọdun 2008.Azor jẹ aṣoju ofin fun aṣọ Energy Resources Ltd ti o wa ni Abuja fun ọdun meji (2008-2010).ni ọdun 2011, o dije fun ipo olori awon obinrin ni ipinle Naijiria labẹ ẹgbẹ Congress for Progressive Change (CPC), o si wọle.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó di Senato fún ìpínlẹ̀ Anámbra lábẹ́ ẹgbẹ́ APC.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kokanlelogun osu kejo, odun 2019, Aare orile-ede Naijiria, Muhammadu Buhari fi se Minisita lori Oro Ayika ni orile ede Naijiria.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
TÍ WỌ́N BÍ LỌ́DÚN 1994 jẹ́ gbajúmọ̀ àkàndá abarapá ọmọbìnrin ayàwòrán tí kò lọ́wọ́ àti ẹsẹ̀, ṣùgbọ́n tí ó ń ṣiṣẹ́ ọnà lára ọ̀tọ̀.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ abarapá ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkìtì tí ó máa ń rìn pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ìjókòó-ìrìnnà(WHOyOGAB). Ewe àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé Bọ́sẹ̀ ló ti ní ìṣòro, ṣùgbọ́n kò gbà kí èyí mú un já kulẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí Bọ́sẹ̀ bí i ni abarapá tí kò lẹ́ṣẹ̀ àti ìka-ọwọ́.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ tí ìyá rẹ̀ sin jẹ́ oǹsoro láti Ìpínlẹ̀ Ẹ̀kìtì lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bose ko ka ju ipele keji lọ ni ile-iwe akobere nitori ipo abarapa ti o wa.. | wikipedia | yo |
Láti kékeré ni ó ti ṣe àwárí ẹ̀bùn àfọwọ́yàwòrán, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ní ìka ọwọ́.. | wikipedia | yo |
Ọpọlọpọ sin ni aworan awon eniyan ńláńlá ti o ti ya.Aṣayan awon ise re aworan afọwọya Davido aworan afọwọya Joshua Joshua aworan afọwọya Gomina Kayode Lowaye aworan afọwọya DJ Cuppy aworan afọwọya olorin fuji, Obesere aworan afọwọya Dpe Osinbajo aworan afọwọya Felix eireo Okanna aworan afọwọya taraji p Henson Davido and Chioma; CEO, oracle experience Agency, Dr.. | wikipedia | yo |
Adepéjú olùkókun (kokun foundation ); wife of Nigeria Vice President, Dolapo Osinbajo; DJ Cuppy; Taraji p Hensonawon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Bola Odelékè tí wọ́n bí lọ́dún 1850 jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run, ajíyìnrere Nàìjíríà àti bíṣọ́ọ̀bù obìnrin àkọ́kọ́ ní Áfíríkà.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile ijo Power Pentecostal Church.Igba ewe rẹodelékè jẹ ọmọ bibi Ilu Ibadan, ni Ipinle Oyo lorilẹ-ede Naijiria.O kawe akobere ati ipele keji ni Ileṣa ni Ipinle Osun, ilu Mama to bi i lomo.O di onigbagbọ omoleyin Jésù lodun 1970,sugbon odun 1974 lo bere ise lobinrin, ti o sin se ajoyo ogoji odun ti o bere ise Ọlọrun lodun 2014.O gboye bíṣọ́ọ̀bù lodun 1995,Oun sin ni bíṣọ́ọ̀bù obinrin akoko ni ile Afirika.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Sandra Chidinma dúrú-Eluobi jẹ onisowo ati oludasile Pre-adult Affairs organization.Oun ni alakoso ile ise Sanchhy Nigeria limited, Zst media and entertainment ati executives Cable and eleLásárù company.. | wikipedia | yo |
O jẹ onimọran fun standard organization, police women units, police service Commission ati Kulfana Mining company.. | wikipedia | yo |
O ko ipa rìbìtì ninu bii Rochas Okorocha se di gomina ipinle Imo ni odun 2011.. | wikipedia | yo |
Ni ọdún 2013, ó gbìyànjú lati dá ẹgbẹ́ òṣèlú tirẹ̀ kalẹ́, ki ó bà lè díje fún ipò gómìnà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó dá ètò bare it out! with Sandra dúrú.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2014, AmBasedo Naijiria fun orile-ede Ivory Coast fun ni ami eye fun ipa ti o ko lati wa atunṣe fun iṣoro àìníṣẹ́, ija ati bi o se pese eko fun awon omo Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó gbé ètò tuntun kan kalẹ̀ tí ó pè ní The Up Project.Ní ọdún 2014, ó fẹ́ Emmanuel Ẹbubuka Eulobi tí ó jẹ́ agbábọ́, wọ́n sì bí ọmọkùnrin kan ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2016.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Sarah Ládípọ̀ Manyíká (bíi ní ọjọ́ keje oṣù kẹta odún 1968) jẹ́ òǹkọ̀wé ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni Olùkọ̀wé in dependence (2009) àti like a múlẹ̀ obì ice ẹlòmíràn to the sun (2016).. | wikipedia | yo |
Ìwé Manyíká farahàn ninu ìtàn àkọlé àwọn ọmọbinrin titun ní ilẹ̀ Áfríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé ati Èkó rẹ̀ wọ́n bí Sarah Manyika sí ìlú Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O ti gbe ni orile ede Kenya, France, Zimbabwe ati Britain.. | wikipedia | yo |
sáùdátú Mámahdi (bíi ní ọjọ́ ogún, oṣù kẹrin ọdún 1957) jẹ́ ajàfẹ́tọ́ fún àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni akọ̀wé fún ẹgbẹ́ Women's Rights Advanment and Protection Alternative (WAPA).. | wikipedia | yo |
O ti kọ ìwé tí ó lé ní ogún lórí bí ìyà ṣe n jẹ àwọn obìnrin.. | wikipedia | yo |
Mahdi ni o jẹ adari fun awọn to parapo lati ja fun obinrin ti wọn fẹ pa nitori wipe o bi ọmọ lai se igbeyawo.ibẹrẹ pẹpẹ aye ati eko rẹ won bi Mahdi ni ojo ogun, osu kerin odun 1957 si ipinle India ni Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1964, ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ Kaduna Central Primary School.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1970, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queen Amina College ní Ìpínlẹ̀ Kaduna.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1978, ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Ahmadu Bello University ní ìpínlẹ̀ Zaria.Iṣẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bi olùkọ́ ní ilé ìwé ṣáájú kí ó tó kọ̀wé ìposílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù kẹjọ ọdún 1989, ó di olórí ilé ìwé Government Girls Secondary school ní ìpínlẹ̀ Bauchi.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1995, wọ́n fi ṣe alákòóso ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Abubakar tàtàrí Ali Polytechnic ní Bauchi, ó sì di ipò náà mú títí di ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1998 tí ó wá fi iṣẹ́ náà sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
O je Akowe Gbogbogbo fun egbe Women's Rights Advanment and Protection Alternative (PAWA).ami eye ni ojo Kẹẹ̀ta osu Kọkànlá odun 2011, Aare orile ede tele ri, Goodluck Jonathan fun ni ẹbun National Honours Award.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Salamatu Husṣàìní Suleman jẹ agbemọsọ ti o si jẹ Komisona lori ọrọ oṣelu, alaafia ati abo fun ẹgbẹ gúnọn.. | wikipedia | yo |
Ni osu kejila odun 2008, won fi je Minisita lori Oro obinrin ati idagbasoke Ilu.ibẹrẹ pepe aye ati Eko re won bi Salamatu Husini Suleman si ilu Argungun ni Ipinle Kebbi.. | wikipedia | yo |
Baba rẹ̀ jẹ́ adájọ́, ìyá rẹ̀ sì wá láti ìdílé ọba ní Gwàdà.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Ahmadu Bello University ní ìpínlẹ̀ Zaria, ó sì gboyè nínú ìmọ̀ òfin.Iṣẹ́ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú Ministry of Justice ní Ìpínlẹ̀ Sokoto.. | wikipedia | yo |
Lẹhinna o ṣiṣẹ pẹlu Ile ifowopamọ Continental Merchant Bank ni Ilu Eko fun ọdun meje.. | wikipedia | yo |
O sise pelu nal Merchant Bank fun igba die ki o to lo si ile ise aluminium fójúter company nibi ti o n ti se onimoran ofin fun won.Aare orile edeNaijiria tele, Umaru Yar'Adua fi Suleman je Minisita lori Oroawon obinrin ni osu pelu osu itọkasi odun itọkasi.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Adenike EpeOLUWA Oyak (Bii ni ojo karun-un, osu karun-un ọdun 1931) je oloselu ti o gbajumọ gege bi Minisita binrin akoko ni orile ede Naijiria, o si gboye naa ni ọdun 1979.oya je omo ile Igan Alade ni ilu Yewa North ni Ipinle Ogun.. | wikipedia | yo |
O si ṣe gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ní àwọn ilé Ìkẹ́kọ̀ọ́ ní Ìlú Yewa àti Mushin.. | wikipedia | yo |
Ni odun 1960, o lo si oke okun lati ni imo ninu iṣiro owo.oya darapo mo Federal Civil Service ni odun 1963 leyin ti o pari eko re ni orile ede United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1979, ó di Mínísítà gégé àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láá ìso Shehu Shagari.. | wikipedia | yo |
O di AMbasedo ti Naijiria fun awon orile orile ede United Mexican States of Panama, Costa Rica atii Guatemala.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Amina Mama (tí a bí ní Ọjọ́ kọkàn Oṣù Keta-an Ọdún1958) jẹ́ oǹkòṣe, Àjàsọ́nà àwọn obìnrin àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Àwọn ǹ kan tí ó dojukọ́ gangan ní àwọn ǹ kan tí ó jẹ mọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ lẹ́yìn ìjọba amúnisìn, ti ológun àti ti abo.. | wikipedia | yo |
Amina ti gbé ní orílẹ̀-èdè Áfíríkà, Yúsí, àti Ariwa Amẹ́ríkà àti wípé ó ti ṣiṣẹ́ láti mú ìbáse láàrin àwọn onísin àti olóyè obìnrin káká àgbáyé.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé e rẹ̀ á bí Mama ní apá Ariwa orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Nàìjíríà ní ọdún 1958 ní ìdílé aládà.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí Mama ti sọ, ó ní Ìpínlẹ̀ Ìdílé òun àti bí wọ́n ṣe tọ́ òun dàgbà ti mú kí òun ṣe àgbékalẹ̀ ìyeye ìgbéayé òun.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1992, o ṣe igbeyawo pẹlu Nuòjijìdin Farah ẹni ti o bi ọmọ meji fun un.. | wikipedia | yo |
Amina Mama dàgbà ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná, níbití oníurùuru ẹ̀yà àti ẹ̀sìn gbé wà, ní apá Ariwa orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ọpọlọpọ ninu awọn mọ̀lẹ́bi Mama ni wọn kó ipa ninu idagbasoke eto ẹkọ ti agbegbe wọn lẹ́yìn ìjọba amúnisi.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1966, o fi agbegbe rẹ ti o n gbe ni orile-ede Naijiria silẹ nitori rògbòdìyàn ti o tako Musulumi.Iṣẹ ẹ rẹ Mama kuro lati orile-ede Naijiria lo si orile-ede Gẹẹsi lati tẹsiwaju ninu eko o re ni Yinifasiti ti St.. | wikipedia | yo |
Andrews tí ó wà ní ìlú Scotland, ní ọdún 1980 níbi tí ó ti gba oyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ lórí i Psychology, àti ilé-ìwé ìmọ̀ nípa ọ̀rọ̀-Ọjà àti Ìmọ̀-ọ̀rọ̀ Òṣèlú ní Yunifásítì ìlú London ní ọdún 1981 níbí tí ó ti gba oyè ẹlẹ́ẹ̀kejì nínú ìmọ̀ lórí Social Psychology.. | wikipedia | yo |