cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ní ọdún 2010, àwọn African Union fi ṣe AmBasedo fún àlàáfíà àti Abo ní ilẹ̀ Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kìíní Ọdún 2009, Alya di ikan lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ ppR Foundation for Women's dignity and Rights.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn ẹgbẹ́ ajìjàgbara fún àwọn obìnrin tí ó wà ní stop FGm now, together for African women,end FGm.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kokanla osu kesan-an odun 2013, Dirie si ile iwosan the Desert flower center.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ keje, Oṣù kẹta ọdún 2019, wọ́n sọ pé wọ́n ma kọ orin nípa ìtàn ayé rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní Ọjọ́ kejìlélógún oṣù Kejì ọdún 2020, wọ́n gbé orin náà jáde.Àmì ẹ̀yẹ Woman of the Year Award (2000) láti ọ̀dọ̀ Glamour Magazine. | wikipedia | yo |
Prix des Generations (2007) lati ọdọ World Demoètò Association. | wikipedia | yo |
Martin Buber Gold Medal lati Odò EUriade Foundation (2008).. | wikipedia | yo |
Gold Medal of the President of the Republic of Italy (2010) . | wikipedia | yo |
Thomas Detyl Prize (2013) International Freedom Prize (2014) Women for Women Award (2017), Awarded in Vienna by The Magazine “Look! Donna Dell' (2018) In Italy ~ million Chances Award (2018) Sunhak Peace Prize (2019).ìgbésí aye rẹ Dirie di ọmọ orilẹ ede Australia ni Oṣu Kẹta ọdun 2005.Awọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ó gba oyè-ẹ̀kọ́ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga National School of the Arts Theatre, òun sì ní akẹ́kọ̀ọ́ tó peregedé jùlọ láàrin àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀.Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀ ní àkókò ìgbà tí Xolile wà ní ilé-ẹ̀kọ́ National School of the Arts Theatre, ó ní ànfààní láti ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Thembi Mtshali-Jones, ẹnití ó padà dà gẹ́gẹ́ bi alámọ̀ràn rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn méjéèjì dìjọ kópa nínu eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Crucible.. | wikipedia | yo |
Xolile tún ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù tó fi mọ́ eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Soul City, níbi tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi Zama.. | wikipedia | yo |
Ó tún ti kópa nínu eré "Another Child." Ọdún 2002 ni ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Generations.. | wikipedia | yo |
Ó kópa gẹ́gẹ́ bi 'Julia Montene' nínu eré náà láti ọdún 2002 sí 2005.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2007, ó darapọ̀ mọ́ àwọn olùkópa ti eré NCIS nígbà tí eré náà dé apá kaàrún tó síì kópa gẹ́gẹ́ bi 'Sayda ZuriOfiri | wikipedia | yo |
Lara awon ere telifisonu miran ti o tun ti se ni Secret in My Boso, Scoop Schoombie, Justice for All, Isidingo ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.Ni opolopo igba ni won ti yàán fún àwọn àmì-ẹ̀yẹ níbi àwọn ayẹyẹ ẹ̀yẹ, pàápàá jùlọ àwọn ayẹyẹ ẹ̀yẹ tí ó jẹ́ ti orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Golden Horn Awards fún ipa rẹ̀ nínu eré Generations.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, wọ́n tún yàán fún àmì-ẹ̀yẹ kan náà níbi ayẹyẹ Golden Horn Awards bákan náà fún ipa rẹ̀ nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Fallen.Àṣàyàn àwọn eré àkò Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1977.. | wikipedia | yo |
Malaika ùwamátabi (bíi ní ọdún 1990) jẹ́ oṣere, akewi, olórin ati ajìjàgbara lórílẹ̀ èdè Rwanda.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé rẹ̀ wọ́n bí màláíkà sí Rwanda ní ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Nitori iṣẹlẹ ti o waye ni ọdun 1994, oun ati iya rẹ sa kuro ni Rwanda lo si Uganda.. | wikipedia | yo |
O gboye ninu imo ere ori itage lati ile eko giga ti Fordham University.Iṣẹ o kopa ninu ere Loveniass Generation eyi ti Tomás Petkovski gbe kale ni ọdun 2018.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún náà, ó ṣe bí Princess nínú eré Yankee Hulóró.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó farahàn nínú eré Our Lady of the nílé.. | wikipedia | yo |
Ipa tí ó kó nínú eré Miraclemith in Rwanda ni wọ́n fi yàán fún àmì ẹ̀yẹ Best Solo performance ní Viv Award ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ó wà lára àwọn tó dára níbi ayẹyẹ DanceAfrica event ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ìkan lára àwọn obìnrin tí wọ́n pè láti sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ Forbes Woman Africa 2020 leading Women Summit tí wọ́n ṣe ní South Áfríkà.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Thembi Mtshali-Jones (tí wọ́n bí ní 7 Oṣù kọkànlá, Ọdún 1949) jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù bíi Sgudi 'Snaysi, Stovel, Silent Witness àti Ọláilawú.. | wikipedia | yo |
Ó tún máa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ní Global Arts Corps, èyí tí ó wà ní Kosovo.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí Thembi ní 7 Oṣù Kọkànlá, ọdún 1949 ní abúlé Sabhoza nítòsí Uldi ní ìlú Durban, orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Kòpẹ́ sí ìgbà tí wọ́n bí ni àwọn òbí rẹ̀ kọrawọn sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó dàgbà ní ìlú Kwamas níbití ó ti ní àwọn ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó fi ilé-ìwé sílẹ̀ lẹ́hìn tí ó lóyún sínú.Ó ní ọmọ obìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Phumzile, èyí tí ó bí fún ọkọ àkọ́kọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Orúkọ ọkọ èkejì rẹ̀ ń ṣe Emrys Jones, ẹnití ó kéré sí Thembi lọ́jọ́ orí.. | wikipedia | yo |
Àwọn méjèjì pàdé nígbà tí Emrys wá láti wo eré tí Thembi dánìkan ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ A Woman in Waiting.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gbé papọ̀ fún ọdún mẹ́tàdínlógún títí di ọjọ́ ikú Emrys ní ọdún 2016.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ Thembi kópa nínu eré Welcome Msomi kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Umabatha.. | wikipedia | yo |
Lẹhin naa lo darapọ mọ ẹgbẹ akọrin kan to si pada di asiwaju nibẹ gẹgẹ bi 'Mama tembumẹwa | wikipedia | yo |
Ó lọ sí orílẹ̀-èdè USA láti tẹ̀síwájú iṣẹ́ orin rẹ̀, níbẹ̀ ló ti pàdé àwọn gbajúgbajà akọrin mìíràn tí orúkọ wọn ń ṣe Hugh Masekela àti Miriam Makeba, tí wọ́n síì di jọ ṣe eré orin káàkiri ilẹ̀ Yúróòpù àti Áfríkà fún àwọn ọdún bíi mélòó kan.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1987, Thembi padà sí Gúúsù Áfríkà, ó síì darapọ̀ mọ́ ilé-ìṣeré Market Theatre.. | wikipedia | yo |
Ní ilé-ìṣeré náà ló ti ní ànfààní láti ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Janice Honeyman nínu eré Black And White Follies.Láti ọdún 1970, ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré orí-ìpele.. | wikipedia | yo |
Òun pẹ̀lú Gcina Mhlophe àti Maralin Vanrenen dìjọ kọ eré kan tí wọ́n sì tún kópa nínu eré náà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Have You Seen Zandile.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ kan níbi ayẹyẹ Edinburgh Festival Fringe fún ipa rẹ̀ nínu eré náà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn náà, ó tún fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lúBarney Simon láti dìjọ kọ eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Eden and other Places and Women of Africa.Àṣàyàn àwọn eré rẹàwọn Ìtọ́kasíàwọn Ìtàkùn Million Discography of Thembi Mtshaliàwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1949.. | wikipedia | yo |
Blandine Yameogo (tí wọ́n bí ní ọdún 1960) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Bùrkínà Fasọ̀.. | wikipedia | yo |
O ti kopa ninu ọpọlọpọ awọn fiimu to lorukọ to fi mo La nuit de la Verité, Delwende ati Notre etrangere.. | wikipedia | yo |
O tún maa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí onijo.Àṣàyàn àwọn eré ̀bàko ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1960àwọn ènìyàn òkẹrin.. | wikipedia | yo |
lételọ Micael (tí wọ́n bí ní ọdún 1997) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi 'Awet' nínu fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Feuerherz.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ní ọdún 1997 ní ìlú Asmara, orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí ó kópa nínu eré ológun tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní Feuerherz, àwọn ènìyàn kan fi ìwé ránṣẹ́ sí àwọn ẹbí rẹ̀ láti ṣe wọ́n ní ìjà, èyí tí ó mú kí àwọn ìjọba orílẹ̀-èdè kan ní ilẹ̀ Yú ṣe ètò àbo fún wọn.Iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2008, Micael kópa nínu eré tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní Feuerherz lọ́mọ ọdún mẹ́wàá.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kọ́kọ́ gbé fíìmù náà jáde ní ọjọ́ 25 oṣù kẹẹ̀sán ọdún 2008.. | wikipedia | yo |
Fíìmù náà dá lóri ogun tí orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à jà pẹ̀lú Ethiópíà láti gba òmìnira.. | wikipedia | yo |
Àwọn ènìyàn sọ dáada nípa fíìmù náà tí wọ́n sì tún gbóríyìn fún Micael fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi 'Awet'.àṣàyàn àwọn eré rẹ̀àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1997àwọn ará Bùrkínà Fasọ̀àwọn ènìyàn Alààyè tí | wikipedia | yo |
Tariro Washe Mnangagwa (tí wọ́n bí ní ọdún 1986) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Sìmbábúè.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré kan tí ọdún 2020 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Gonarezhou.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn ọmọ obìnrin Ààrẹ orílẹ̀-èdè Sìmbábúè lọ́wọ́lọ́wọ́ ti orúkọ rẹ̀ n ṣe Emmerson Mnangagwa.Ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi Tariro ní ọdún 1986 ní orílẹ̀-èdè Sámbíà.. | wikipedia | yo |
Òun ni ọmọ obìnrin àbígbẹ̀yìn nínu àwọn ọmọ mẹ́fà ti àwọn òbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Jayne Matarise di olóògbé ní 31 Oṣù Kínní, Ọdún 2002 látàrí ààtan jẹjẹrẹ kan.. | wikipedia | yo |
ati àwọn ibeji ti wọn ṣe Sean ati Collins.Iṣẹ iṣẹ rẹ Tariro gba oye-ẹkọ ninu imọ fọtoyiya lati ile-ẹkọ giga kan ti o wa ni Ilu Cape Town.. | wikipedia | yo |
O tun gba oye-ẹkọ miran ninu imo iṣakoso ere idaraya lati ile-ẹkọ gigacape Peninsula University of Technology.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí ó padà sí orílẹ̀-èdè Sìmbábúè, Tariro darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Akasga, ẹgbẹ́ kan tí ó n rí sí Dídáàbò Bo àwọn ẹranko orí-ilẹ̀ àti inú-omi àti láti tako Didede àwọn ẹranko náà lọ́nà aito.. | wikipedia | yo |
O pada tun darapọ mọ from ẹgbẹ naa ti agbaye, eyi ti wọn pe ni International Anti-Popo Foundation.laipẹ jọjọ si dídárapọ̀ rẹ mọ́ ẹgbẹ agbaye naa, wọn pee lati wa kopa ninu ere ti akọle rẹ jẹ Gonarezhou, eyi ti oludari ere Sydney Taivavashe ṣe, ti aájò Zimbabwe Parks and Wildlife Management Authority sii ṣe onígbọ̀wọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Tariro kópa gẹ́gẹ́ bi 'Sergeant Onai' nínu eré náà.Àṣàyàn àwọn eré àkò Ìtọ́kasíàwọn ẹita ìjád Litmus Test for filmmakers' ìṣed ed's Daughter Stars in award winning anti-PoLOS filmàwọn Ọjọ́ìbí ní 1986àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
ìjìd Ibrahim zarrouk (, bíi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní ọdún 1980) jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè Tùnísíàìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi Env sí ìlú Tunis.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ ni Ibrahim Alaukuk, baba ìyá rẹ̀ sì ni Ali Zllow tí ó jẹ́ òṣèlú.. | wikipedia | yo |
Baaliu gboyè nínú ìmọ̀ òfin àti òṣèlú láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Saint Joseph University ní Lẹ́baọ́n ní ọdún 2003.Iṣẹ́ Env bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 1997.. | wikipedia | yo |
Ere Ori Oriwe tí ó ma kọ́kọ́ ṣe ní orílẹ̀ èdè mìíràn pàkò sí Tùnísíà ní Fares Bánì Marwan ní orílẹ̀ èdè Syria ní ọdún 2004.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn eré tí ó ti ṣe ní Al Mosafer, Tisbah Ala Khair àti Sheikh Jackson.Ìgbésí ayé rẹ̀ Env fẹ́ Aqys Muk ní ọdún 2012.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, ó ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú irinper Saad.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Danieline Moore Kamya jẹ oṣere ati oniṣowo lorilẹ Ede Liberia.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2007, o di Omidan Liberia.Iṣẹ ni ọdun 2006, o lo fun idije Omidan Liberia ti Amẹrika ṣugbọn o gbe ipo kẹrin nibẹ.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún tó tẹ̀le, ó tún kópa nínú ìdíje náà, ó sì gbé ipò kìíní.. | wikipedia | yo |
O kopa ninu ere Crazy in Love pẹlu awọn oṣere bii Jim Iyke, Altorrọ Black ati Crystal Milan.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludari nalu cofrẹ ati Glitz by nalu.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Rym Saidi Breidy ránfin(Bii ni ojo kokanlelogun osu kefa odun 1986) je modeli ati osere lórílẹ̀-ede Tùnísíàise Rym Breidy bere ise gege bi modeli ni odun 2003 lehin ti o gbe igba orókè nibi idije elite Model Look Tunisia.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006, ó gbé ipò kìíní níbi ìdíje mission fashion.. | wikipedia | yo |
O ti si ṣe gege bi Rori fun Profile Models ni London, Women Model Management ni Milan, MP Management ni Paris, One.1 Management ni New York City, Munich Models ni Germany, MPLE, A mega ní Miami... | wikipedia | yo |
O gbajumọ ni Italy fun ipa Madre Natura ti o ko ninu ere IAO Darwin.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ amákodò fún ilé iṣẹ́ Traveltọ̀dọ̀ láti ọdún 2013.Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù keje ọdún 2017, ó ṣe ígbéyàwó pẹ̀lú Wissam Brei.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ kẹfà àti Kesàn-an ti African Movie Academy Awards.Iṣẹ́ Suya kópa nínu eré Seìdámẹ́wàá of a Life ní ọdún 2010 pẹ̀lú Tap Gwaza gẹ́gẹ́ bi ọmọ ọ̀dọ̀ tí ọ̀gá rẹ̀ ma ń fi ipá bá lòpọ̀.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye oṣere binrin to dara jù lọ lati ọdọ African Movie Academy Awards fun ipa ti o ko ninu ere naa.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, ó kópa nínu eré Last fiShing Boat, ipa rẹ̀ nínu eré yìí ló jẹ́ kí wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ AMAA.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó kópa nínu eré Chenda tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìpọ́njú tí àwọn Àgàn má ń rí.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó gbé eré my wẹ́wẹ́ Story jáde, ó sì kó ipa tàdá nínú eré náà.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Jesesi Mungoshi jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè Zimbabwe.Iṣẹ́ Mungoshi kópa nínu eré African Journey ní ọdún 1989 pẹ̀lú àwọn òṣèré bíi Jason Bstolicker, Katja Bvivi, Allan Jordan àti Ulla Mahaka.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1991, ó kó ipa Néríà nínú eré Néríà èyí ti Godwin Mákẹ̀kẹ̀ gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Oun ati awọn oṣere bii Yemi Goodman Ajibade, ben Daniels, eldinah THatedi ati Frank Windsor jo kopa ninu ere Rwen ti farai 1980sno gbe kale ni odun 1993.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2017, o farahan gẹgẹ bi gógó ninu ere Cook off.. | wikipedia | yo |
Ó gba àmì ẹ̀yẹ Lifetime Achievement Award láti ọ̀dọ ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Great Zimbabwe University ní Oṣù Kẹta ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2020, eré Shaina tí òhun àti Marian kúnga, Charmaine Muila kópa nínu gba ìdun púpọ̀ lọ́dọ̀ àwọn èèyàn.Àṣàyàn eré rẹ̀ìgbésí ayé rẹ̀ Jesesi jẹ́ ìyàwó fún Charles Mungoshi tí ó kú ní ọjọ́ kẹrìndínlógun Oṣù Kejì ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí ọmọ márùn-ún àti ọmọ-ọmọ méje kí ọkọ rẹ̀ tó kú.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Henrietta Mbawah jẹ́ òṣèré àti Atàtà lọ́lẹ̀-èdè Sierra Leone.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi olùdarí eré eré Ìdíja àti fún ipa tí ó kó nínú eré Ebola Checkpoint.Iṣẹ́ ní ọdún 2016, mbáwah gbé eré ran pé Barja kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Eré náà sọ̀rọ̀ nípa ọmọbìnrin Barvtu tó ṣẹ́gun àrùn Ebola ní Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún náà, ó kó ipa oníròyìn nínu eré Ebola Checkpoint.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó gba àmì ẹ̀yẹ Sister's Choice Award.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Zainab Jah jẹ́ òṣèré orí ìtàgé, Oriwewe àti fíìmù lórílẹ̀-èdè Sierra Leone.. | wikipedia | yo |
Ó gbajúmọ̀ fún ipa Maima tí ó kó nínú eré eClíp-Se.. | wikipedia | yo |
Ó kó ipa Aminata Sissoko nínú eré deep state àti Aby Bahbah nínú eré Homeland.... | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó tayọ jùlọ ní ọdún 2019 láti ọ̀dọ Drama Desk Award.Àṣàyàn eré àko Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Adewale "Wally" Adeoye (won bi í lodun 1981) je aare akoko fun ajo-asaA, Obama Foundation ti Aare ana orile-ede Amerika, Barack Obama da sile.. | wikipedia | yo |