cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
during the Obama administration, Adeìyàn ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi igbákejì olùdámọ̀ràn lórí ẹ̀tọ́ àbò fun Àjọ Ètò Ọrọ̀-Ajé Àgbáyé,International Economics lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 2015 sí 2016, bẹ́ẹ̀ náà oun ni igbá-kejì ọ̀gá àgbà ti National Economic Council.Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀adéyè dàgbà sí Los Angeles, California..
wikipedia
yo
O kawe gboye Bachelor of Arts lati University of California, Berkeley ati Juris Doctor lati Yale Law School.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
AUST Nóàh Abrams tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì Oṣù Kẹ́kẹ́ ọdún 1996 jẹ́ òṣèré ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré onípele Àtìgbà-dègbà gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà-ìtàn Ron Anderson nínu ìpele ẹlẹ́̀ńn ún eré The Walking Dead (2015-2016) tí ó sì tún kópa nínu eré Eutcharia gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà ìtàn Ethan Lewis..
wikipedia
yo
O je omo eya WW.Iṣẹ Costing ni o kopa gege bi eda itan Ron Anderson ninu ere AMC the Walking dead ninu ipele karùún ati ipele kefa ere naa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, ó tún kópa bí u eré tí ọ̀gbẹ́ni Kyle wílawski's kọ tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ All Summers End, tí ó sì kópa gẹ́gẹ́ bí “hunter Gors"Ní ọdún 2017, Abrams tún kópa gẹ́gẹ́ bi “Troy” nínú eré Elirĩ Brad's status..
wikipedia
yo
O tun ko ipa to po ninu ere SCary Stories to Tell in the Dark ni ọdun 2019..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2020, ó kópa gẹ́gẹ́ bi olú-ẹ̀dá ìtàn nínu eré Chemical Hew.Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀eré orí amóhù-máwo Ìtọ́kasí ìjáde àwọn Ọjọ́ìbí ní 1996àwọn ènìyàn ÀGudá-Century American Mabo Actor From Saraṣọ̀tá, Flori Mamasta Mata Actor Actor Male Television Actors American American Actors Actors Kan Fete Ggi..
wikipedia
yo
Asher chart Ángel tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹsànán ọdún 2002 jẹ́ òṣèrékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2008 níbi tí ó ti kópa nínu eré Jolene, eré tí Jessica ChaStain náà ti kópa..
wikipedia
yo
O di ilu-mooka latari ipa re ti o ko gege bi "Jonah Beck" ninu ere onípele Disney Channel ni odun 2017..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, Angel kópa gẹ́gẹ́ bi Billy Batson nínu eré DC extended Universe Film Shazam!Igbe àyè kò bí Angel ní ìlú Phoenix, Arizona, ó sì n gbé ní ìlú Paradise Valley, Arizona..
wikipedia
yo
Awon obi re ni jody ati Coco Ángel, oun si ni o je akobi omo won..
wikipedia
yo
Ó tún ma n kọrin tí ó sì ma n ta jìá.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèréAngel kókó fara hàn nínú eré Jolene nígbà tí ó wà ní deede ọmọ ọdún márùn ún ní ọdún 2008, lẹ́yìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínu àwọn eré orírí́n..
wikipedia
yo
nígbà tí yóò fi di ọmọ ọdún méje, ilé-iṣẹ́ Desert stages Theatre gbé ètò ìgbaniwọlé kan kalẹ̀lórí orin kíkọ, pẹ̀lú ìyọ̀ǹda àti ìrànlọ́wọ́ àwọn òbí rẹ̀, ó jáwé olúborí ó sì gbapò kíní..
wikipedia
yo
ìyá rẹ̀ ṣàdéhùn fún wípé òun yóò mú lọ sí ìlú Los Angeles bí ó bá lè tepá mọ́ iṣẹ́ tí ó sì kópa nínú èrè tí ó tó ọgbọ̀n..
wikipedia
yo
lára wọn ni the Little Mermaid, Seussical, Mary Poppins, ati into the Woods ni abẹ́ Ile-iṣẹ Desert stages Theatre ti ó wà ní agbègbè Scottsdale..
wikipedia
yo
Iya R mú àdéhùn rẹ̀ ṣẹ,tí ó sì mú Ángel lọ sí ìlú Los ageles nígbà tí ó pé ọmọ ọdún méjìlá..
wikipedia
yo
Angel tún jáwé olúborí nínú ìdíje jonah Beck tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí Enb lọ̀pá nínú Disney Channel àti Andi Mack..
wikipedia
yo
Òun àti àwọn ẹbí rẹ̀ kò losi ìlú Utah láti lè jẹ́ kí ó ma kópa nínú ìdíje tí ó sẹ̀sẹ̀ Moke rẹ̀.Ninu Oṣù Kẹrin ọdún 2019, Angl kópa nínú eré Billy Batson, gẹ́gẹ́ olú ẹ̀dá ìtàn pẹ̀lú Zaàṣeyọrí Levi gẹ́gẹ́ Àgbàlagbà atọ́nisọ́nà nínú eré náà..
wikipedia
yo
Angel gbé orin ẹyọ̀kan ṣoṣo rẹ̀ jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní "One thought Away", Irin tí Wiz Khali, ní ọjọ́ Oṣù Kẹfà Ọdún 2019.Àwọn àṣàyàn eré àko àmì-ẹ̀yẹ àti ÌFISỌRÍ Wà Ìtọ́kasíàwọn ààwọn ládédédé ní 2002 ní 2002 From Phoenix, Arizo Mamas Mago Child Actors American Malelé Actor Eniyan Alààyè From From Valley, Arizona-21st American American Fạs Actors
wikipedia
yo
Iris ApawTo (; tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹwàá ọdún 2002 jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn "Arya" nínu eré onípele tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀.Lórí ìkànì Netflix tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Love, òun náà ló tún kópa ẹgẹ bí ẹ̀dá ìtàn "CharlotteCharlotte" nínú eré knocked Up àti This is 40.Igba Ewe rẹ̀apáto ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2992, àpawTo tí ó jẹ́ ọmọ gbajú-gbajà òṣèré judd àpaw, tí ìyá rẹ̀ Leslie Mann náà sì jẹ́ òṣèré pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Her maternal great-grandmother of Finnish Ancestry.Iṣẹ́ rẹ̀ó di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó bi gẹ́gẹ́ bi nínú eré Rèbékàri lọ́hùn up, eré tí baba rẹ̀ ju apáTo Tow darí rẹ̀..
wikipedia
yo
Lara awon ere onípele ori ero amole-máwòrán ti o ti kopa bi "ARYA" ni Love.Awon aṣayan ere refọ̀ràn orinawon itọkasiawon irin ìjásóde awon Ọjọ́ìbí ni 2002-21st American Actres from Caliph Calia of Finnish descenTÁ Child Child Actres Film Act People People of Finnish descence People of Jewish descenYè Fani Act Meresses Child Act in AltunPlace of Birth Missing (Living People Metunde) Child Act
wikipedia
yo
Ariane Betor ti won bi ni ojo osu kerinla osu kewaa odun 1998, je wíwọ̀n omo orile-ede Amerika ti o di ilu-mooka fun ipa re ti o ko ninu ere Hulu ti o je ipele run runys bi gert Yorke Ìrètí Ewe Wori obi re je omo jew theire re Libe ba osere naa je osere ori-itage.Iṣẹ rearila bere.sise ni igba ti o wa ni omo odun meta, amo ti o mu ise naa ni ọ̀kúnkúndùn ni igba ti o di omo odun mẹsan an..
wikipedia
yo
Ó ti kópa nínu àwọn eré orírírí àti àwọn àwo orin onírúurú bíi The Love-Lọ́tì.Ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi gert Yorkeskes nínu eré Runaways, tí wọ́n kọ́kọ́ gbé jáde ní Hkò́n..
wikipedia
yo
Ó tún kópa bi Carmen nínú eré One Day at a Time.Igbe ayé rẹni inú oṣù Kọkànlá ọdún 2016, Boodr fi lédè wípé ènìyàn Onilo A-ṣakọ ní òun ni orí ìkànnì Twitter rẹ̀..
wikipedia
yo
and has given their casalouns as 'They/them' on their Instagram Profile, indicating they are non-Ifẹ̀.Awon aṣayan ere.re.ere.ori. amo-máwòrán-Awon itọkasiawon Ìtàkùn ìjásóde awon Ọjọ́ìbí ni 1998-21st American Actressestv-Century American singers21st-Century American Women singersamerican Child Actresngomerican People of Mexican descenascan People of Mexican-Jewish descenascan Television Actresses American Actresses Act Actresses Hispanic and pè American People Ènìyàn Alààyè of Birth Missing (Living People)LGBT Jews 🙂
wikipedia
yo
Sofia Black-d'Elia tí wọ́n bí ní inú Oṣù kejìlá ọdún 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mooka látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dà ìtàn tea Marvelli nínú eré skins, sage Spence nínú eré Gossip girl ati Andrea Cornish nínú eré The Night of..
wikipedia
yo
Laarin odun 2017 si 2018 Black-D'Eli kopa gege bi Sabrina ninu ere Fox ati ere Nevriin kan The Karun.Igba Ewe Koba bi Black ni ilu Clifton, ní agbegbe New New Jersey, ní ìrilẹ̀-ede Amerika..
wikipedia
yo
O kẹkọọ jade girama ni Ile-ẹkọ Clifton High School..
wikipedia
yo
Iya rẹ Eleanor, n ṣiṣẹ́ nílé iṣẹ́ ìtẹ̀wé nígbà tí baba rẹ Anthony V..
wikipedia
yo
d'Ég, jẹ adajọ ile-ẹjọ giga julọ ni Ilu New Jersey..
wikipedia
yo
Bàbá rè jẹ́ ọmọ ilé Italy nígbà tí ìyá rẹ̀ he ọmọ ẹ̀yà WW.Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nígbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún márùn ún lásìkò tí ó dara pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ń kọ́ni ní ijó.Iṣẹ́ rẹ̀ nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, ó kópa nínú eré onípele tí All My Children gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn "Bailey"
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, ó kópa nínu eré àkójọpọ̀ àwọn ìgbò wẹẹrẹ ilẹ̀ Britẹni nínu eré tí Eọ̀n pe àkọ́lé rẹ̀ ní Skins, Black kópa nínu eré Gossip Girl gẹ́gẹ́ ẹ̀dà ìtàn SAGE SCce ..
wikipedia
yo
Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà ìtàn Jessie nínu eré Michael Bay tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, Black kópa nínu eré Hel Miniseries the Night of..
wikipedia
yo
She played the role of Sabrina Pemberton on the ọ̀gbìn.’Igbe Aye re New York ni Black-D-O’ fi ṣe ibùgbé.Àwọn aṣayan ere. Ìtọ́kasí Ìtọ́kasí àwon ènìyàn òyan ìkẹrin ní 1991 ní 1991 of Italian descenta Child Child Act Film Act Act Television Television Act Meorace of Jewish Descentclifton High School (New Jersey) alumni from clifton, New Jersect Souse from New 2000se of Italian Descent..
wikipedia
yo
Asher blinff tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kọkànlá ọdún 2008, osereẹ̀kọ́ okùnrin tí ó di ìlú-mọ̀ọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Hotel Transylvania Film Franchise gege bi ẹ̀dà ìtàn Dennis fún ilé-iṣẹ́ Columbia Picturesati Sony Pictures animation.Iṣẹ Reher Bateff jẹ́ ọmọ bíbí Marion àti Saúl Bateff..
wikipedia
yo
Bateff di gbaju-gbaja latari ipa re ti o ko ninu ere Hotel Transylvania 2 nigba ti o wa ni deede omo odun mefa.Iroko reblinffko ni egbon obinrin ti oruko re n je "Meme" ti oun naa je.osere peluawon aṣayan ere reere.ani awon itọkasiawon eniyan eniyan alààyẹ̀American MaAmerican Child Actorsa Malesa Voice Voiceṣàwọn Ọjọ́ìbíṣàwọn ni 2008People from County County, Pennsylvania..
wikipedia
yo
Wema Setu (Bii ni ọjọ kejidinlọgbọn osu Kesan-an ọdun 1990) jẹ oṣere lorilẹ Ede Tanzania.Iṣẹ ni ọdun 2011, o gbe ere Superstar kale ti o soro nipa itan Ife ohun ati diamond Platnum..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2014, oun ati Van Vicker jọ gbe ere Day After Death jade..
wikipedia
yo
Ni odun 2013, o gbe ile ise re kale ti o pe ni endless Fame production.àṣàyàn ere reami eyeawon itọkasi..
wikipedia
yo
Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ AMAA ní ọdún 2019 fún ipa tí ó kó nínú eré náà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
kálä Masanja (bíi ni ọjọ́ kejìlélógún oṣù keje ) jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè Tanzania..
wikipedia
yo
Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ láti ọ̀dọ East Television Award ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú eré kíjíjí cha _*tóther hákì pẹ̀lú Steven KanAndré..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìyàwó fún faraji Chambo.àṣàyàn eré rẹ̀ Kògoso Jehámì là MOMO House Boy Vita bárìdi House Girl & Boy Duluma shortcut BasiLisa You Me and him Devils Kingdomàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Chaste Christopher Inegbedion ti won bi ni agbegbe ilu Muṣin ni Ipinle Eko je gbaju-gbaja oludasile ile-iṣẹ ara eni ọmọ orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile iṣẹ akanṣe ti Creative5.eto-ẹkọ rẹ Christopher lọ si Ile-ẹkọ Yunifasiti Olabisi Onabanjo (oou) ti o wa ni Ipinle Ogun leyin ti pari ile-ẹkọ girama rẹ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ fáfitì, ó dára póò ẹgbẹ́ “Rotary àti “ Lions and Junior Chamber International Familiesíṣe rẹ̀ Christopher jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ International Youth Council, Àjọ tí ó jẹ́ ti gbogbo gbọ́ ènìyàn láwùjọ..
wikipedia
yo
Wọ́n dá àjọ yí sílẹ̀ lábẹ́ ìṣàkóso Youth Assembly at the United Nations ní ọdún 2007..
wikipedia
yo
Pàtàkì iṣẹ́ tí àjọ náà gbé dání ni kí àwọn ọ̀dọ́ lè fohùn ṣọ̀kan lágbàáyé gẹ́gẹ́ bí Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé ṣe gbé kalẹ̀.chaste ni ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n gbé iṣẹ́ àkànṣe Giving Aládúwé kalẹ̀ ..
wikipedia
yo
IṢẸ́ àkànṣe TÍ O níṣẹ PẸ̀LÚ jọméyìn pẹ̀lú àwọn obìnrin láwùjọ..
wikipedia
yo
Oruko ti won nnpe Christopher ni baba oniledi ( "PADEN man") látàrí bi o se ma n pin ilédì fun awon obinrin paa paa julo awon omo obinrin alailẹnikan ki won le roun lo lasiko ti won ba n se nkan osu, ki won si le kẹkọọ nipa pataki lilo ilédì fun idabobo eso obinrin ..
wikipedia
yo
Chaste tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ United Nations Inter-Agency Network on Youth Development's Working Group on Youth and Gender Equality member.chaste tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ìgbìmọ̀ tí ó rí sí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọdébìnrin lágbàáyé ti United Nations Major Group for Children & Youth..
wikipedia
yo
Ó tún kópa nínú iṣẹ́ àkànṣe ti South Africa for the Global Child Forum ní ọdún 2015.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Lena Belkina (ọjọ́ 27 November 1987, Tashkent (Ìṣọ̀kan Sofietí)) jẹ́ olórin ọmọ ilẹ̀ UNAVA.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1987..
wikipedia
yo
Tuntun fún ọmọdé, ilédì tabi ilapọn fún agbá tàbí páádi fún àwọn obìnrin jẹ́ ohun elo kan tí ó ma ń gba omi bíi itọ́ àti ìgbẹ́ ènìyàn dúró lára ọmọ ìkòkò tàbí ọmọdé..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ohun èlò tí àwọn obìnrin ma ń lò láti fi gba ẹ̀jẹ̀ dúró lásìkò tí wọ́n bá ń ṣe ǹkan oṣù, tàbí tí wọ́n bá bímọ, bẹ́ẹ̀ wọ́n ma ń lòó láti fi fi ojú ara àwọn obìnrin tí wọ́n bá ṣiṣẹ́ abẹ fún..
wikipedia
yo
Ó ṣe pàtàkì kí wọ́n má parọ́ ilédì ní àìmoye ìgbà nínú ọjọ́ kan, ìyẹn bí nkan oṣù náà bá ṣe pọ̀ si..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń ṣe ilédì látara àwọn ohun èlò oríṣiríṣi, ìyẹn bí wọ́n bá ṣe fẹ́ kó rí.Ṣiṣẹ́ rẹ̀ṣiṣẹ́ rẹ̀ dá lórí orílẹ̀-èdè tí wọ́n bá ti ń pèsè rẹ̀,tàbí ilé-iṣẹ́ tí wọ́n bá ti ń ṣeé jáde..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà à ń lo ohun-èlò koTex láti pèsè ilédì tí wọ́n ń pè ní Always, equate, àti stayFree..
wikipedia
yo
Tuntun Lil-lets náà wà káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti n sọ èdè Geesi..
wikipedia
yo
Irúfẹ́.Àwọn ilédì tí.A ti mẹ́nu bá yí kò sí fún àwọn aláárẹ̀ tí agbẹ̀du ìtọ́ wọn ti daṣẹ́ sílẹ̀, àmọ́ àwọn mìíràn ma ń lò wọ́n fún irúfẹ́ àwọn aláárẹ̀ bẹ́ẹ̀.ìpínsísọ̀rí rẹ̀Gbé tí ó ṣeé sọnùbí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn olùpèsè àwọn ohun-èlò yí kìí sọ gbogbo ohun tí wọ́n fi pelọ Ọjà wọn jáde, àmọ́ àwọn ohun tí ó gbajúmọ̀ nínú ni bleached rayon, (cellulose made from wood pulp), Òwu àti iké wa..
wikipedia
yo
Láfikún , wọ́n má ń fi turarẹ̀ aládìídùn ati óogu apakòkòrò fojufoju sí..
wikipedia
yo
Láti sọ Ilédì tí wọ́n ti lọ nú, a lè sọọ́ sí inú apó tàbí àkáà ti abọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n wọn lè gbé lọ sí ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ti ń ṣe àtúnrọ àwọn ohun-elo kí wọ́n fi ṣe nkan mìíràn jáde fún lílò.Oríṣiríṣi Ilédì ni ó wà tí a lè sọnù.àwọn ìpòsí
wikipedia
yo
Nkan oṣù, tí a tún mọ̀ sí àlejò obìnrin jẹ́ sísán jáde papọ̀ ẹ̀jẹ̀ àti ikùn tí a ń dá pè ní nkan oṣù ni ònma ń jáde láti inú àpò-Luke tàbí ilé-ọmọ obìnrin gba inú ọ̀bọ jáde..
wikipedia
yo
Nkan oṣù àkọ́kọ́ sábà ma ń bèrè lára ọmọdé tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ ṣe ipò wúndíá tàbí “ọmọge” ní dédé ọmọ ọdún méjìlá sí ọdún mẹ́ẹ̀dógún, àsìkò yí à ń pè ní àsìkò Ìbàlágà.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ṣeé ṣe kí nkan oṣù yí ó tètè bẹ̀rẹ̀ ní nkan bí ọmọ ọdún mẹ́jọ nígbà míràn tí kò sì burú rárá..
wikipedia
yo
Àmọ́ ní àwọn ìlú tí ìdàgbà-sókè wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gbèrú, iye ọjọ́-orí tí ọmọbìnrin lè kọ́kọ́ rí nkan oṣù rẹ̀ máa ń bẹ̀rẹ̀ láti ọdún mẹ́rìndíndlógun sí mẹ́ẹ̀dógún, àmọ́ ní àwọn ìlú tí wọ́n ti gòkè àgbà, ó lè tètè bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
The èròkérò length of time between the first day of one period and the first day of the next is 21 to 45 days in young women, and 21 to 31 days in adults (an average of 28 days).Ṣíṣe nkan oṣù bí nkan oṣù bá ti bere, ó ma ń sábà lọ to ọjọ́ méjì sí ọjọ́ méje gbáko kí ó tó dá..
wikipedia
yo
nígbà tí nkan oṣù kìí wà lára obìnrin mọ́ nígbà tí wọ́n bá ti pé ọmọ ọdún (kúkùn sí àádọ́ta ọdún, àsìkò yí ni wọ́n ń pè ní mẹ́nopọ́ọ̀sì..
wikipedia
yo
Periods also stop during Pregnancy and typically do not résumé during the ini months of breastst.Àwọn alamí nkan oṣùyóò tó ìdá ọgọ́jọ àwọn obìnrin ni wọ́n ma ń ní alamí kan tí yóòa tọ́ka sí bí ara wọn ṣe ń palẹ̀mọ́ fún ǹkan oṣù tí ó ń bọ̀..
wikipedia
yo
in 3 tó 8%, symptoms are severe.Ipò ilera eni tí ó n se nkan àlejòbí nkan àlejò obinrin kò bá ì tíì bere, paa paa julo lara awon Ọ̀dọ́mọdé-binrin ti ojo-ori won ko tii ju odun meedogun lọ, tabi nkan Alrjo ko wa fun bi Àádọ́saan ojo (90 Days), asiko yi ni awon Geesi n pe ni Amealitielidington.Lára awon iṣoro ti o le ro mo nkan alejo obinrin ni inu aworan àpọ̀jù ẹjẹ..
wikipedia
yo
Menstruation in other animals occur in Prites (apes and Monysra).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Narendrabhai DamodarDa Modi ni Minisita Agba India kerinla ati Minisita Agba ti India lọwọ lọwọ lati ọdun 2014..
wikipedia
yo
O jẹ oloselu kan lati BHaratìyá Janata Party, agbari-iṣẹ olùyọ̀ọ̀da ará ilu Hindu kan..
wikipedia
yo
Oun ni Prime Minister akoko ni ita ti ile-igbimọ ti orile-ede India lati ṣẹgun awọn ofin ìtẹ́lẹ̀ra meji pẹlu opojuju to kun ati ekeji lati pari die sii ju ọdun marun ni ọfiisi lehin Erinmàá Bihari Vajpayẹ́ẹ́.igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ ti a bi si idile Gujarati ni Sárénagar, Modi iranlọwọ fun baba rẹ lati ta ta tii bi ọmọde ati pe o ti sọ pe nigbamii o ta iduro tirẹ..
wikipedia
yo
Ó ṣe àgbékalẹ̀ sí rss ní ọmọ ọdún mẹ́jọ, bẹ̀rẹ̀ ìbápọ̀ ìsọ́ pẹ̀lú agbarín..
wikipedia
yo
Modí fi ilé sílẹ̀ lẹhin ti pari ilé-iwé giga ni apakan nitori igbéyàwó ọmọdé si Jashoben Chiman Mol di, eyiti kọ silẹ ti o gba ni gbangba ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọdún sẹhin..
wikipedia
yo
Modì rin kakiri India fun ọdun meji o si ṣabẹwo si ọpọlọpọ awọn ile-iṣẹ ẹsin ṣaaju ki o to pada si Gujarat..
wikipedia
yo
Lakoko ipo pajawiri ti wọn fi paṣẹ kaakiri orilẹ-ede ni ọdun 1975, Modi fi agbara mu lati lọ pamọ..
wikipedia
yo
OURE naa fi i si BJ ni ọdun 1985 ati pe o waye ọpọlọpọ awọn ipo laarin awọn ipo-iṣẹ ẹgbẹ titi di ọdun 2001, dide si ipo ti Akowe gbogbogbo.ibẹrẹ (2014-lọwọlọwọ) Modi dari B€p ni idibo gbogbogbo ọdun 2014 eyiti o fun ẹgbẹ naa ni ọpọlọpọ ninu ile aṣofin kekere ti India, Lok Sabha, akoko akọkọ fun eyikeyi ẹgbẹ kan lati 1984..
wikipedia
yo
Ìjọba mọ̀dí ti gbìyànjú láti gbé idoko-ọwọ́ taara ajeji ni àjẹ́ India..
wikipedia
yo
ati dinku inawo lori eto ilera ati awọn eto iranlọwọ ni awujọ..
wikipedia
yo
Modì tì gbìyànjú láti mú ìlọsíwájú ṣíṣe ní iṣẹ́-ṣíṣe ìjọba; ó ti ní agbára agbedeméjì nípasẹ̀ dídi ìgbìmọ̀ ẹ̀tọ́..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ipolongo imototo ti profaili giga, bẹrẹ ipilẹṣẹ ariyanjiyan ti awọn iwe ifowopamọ ti orukọ giga, ati dinku tabi paarẹ awọn ofin ayika ati iṣe.ni atẹle iṣẹgun ti ẹgbẹ rẹ ni idibo gbogbogbo 2019, iṣakoso rẹ fagile ipo pataki ti jaḿmú ati KaSHMir..
wikipedia
yo
Ìjọba rẹ tún ṣe àgbékalẹ̀ òfin àtúnṣe ti ìlú-ìlú, èyítí o mú kí àwọn ẹ̀hónú jákèjádò jákèjádò orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
Ti a se apejuwe bi imo-ẹrọ iṣe atunṣe oselu si iselu apa-otun, Modi nọmba ti ariyanjiyan ni ile ati ni kariaye lori awon igbagbọ ti orile-ede koko ati ipa ti ipa ti o fi esun kan lakoko awon rúdurùdu 2002, ti a tọka si bi ẹ̀ri ti eto iyasọtọ iyasoto.Awon itọkasi awon oloselu ara indimeje Ọjọ́ìbí ni 1950..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Jaekel jẹ́ ilé alájà méjì òyìnbó amúnisìn tí ó wà ní ìlú Èbúté mẹ́ta, ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́ ilé náà ní ọdún 1898 sí orí ilẹ̀ tí ó pọ̀ kan tí wọ́n sì sọ ilé náà ní orúkọ olóògbé Francis ìgòekel ọbẹ̀ tí ó jẹ́ alámòójútó àgbà fún ilé-iṣẹ́ rélùwéè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó fẹ̀yìn tì ní ọdún 1970..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ ilẹ̀ sísẹ̀èkél yi ni ó jẹ́ ilé àdá àgbà tẹ́lẹ̀ ṣáájú kí wọ́n tó yí padà sílé àwọn òṣìṣẹ́ àgbà..
wikipedia
yo
Oluyaworan Ilé Ọ̀jọ̀gbọ́n John Godwin ni ó tún ilé náà ṣe pẹ̀lú ìfọwọ́ṣowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́ àjọ rélùwéè ní ọdún 2010.Wọn ti sọ ilé náà di ilé Ìṣèdínlógójì kékeré tí wọ́n fi àwọn nkan bí àwòrán àwọn lààmì-laaka, àwòrán àwọn agbègbè oríṣiríṣi , àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ti wáyé ṣáájú òmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lẹ́yìn òmìnira ayé ijọ́un láti ọdún 1940 sí ọdún 1970 síbẹ̀, àti àwọn irinṣẹ́, ohun-èlò, aṣọ oríṣiríṣi àti àwọn àwòrán ọlọ́kan-ó-jọ̀kan tí ó jẹ mọ́ ilé-iṣẹ́ àjọ rélùwéè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n ṣe lọ́jọ́ síbẹ̀..
wikipedia
yo
Ile yi naa tun ile alo nipa igbeyawo kan ni Ipinle Eko.Awon itọkasiawon Ìtàkùn ìjásódegun in LagosMuseum in Lagos19th-century àìríments in Lhamural completed in 1898 dissatismentsments in NigeriaBritish mífi Architecture Eyo and structures in NigeriaHistoric House Fs In Nigeria..
wikipedia
yo
Broad Street jẹ opopona kan ti o wa ni Lagos Island, ti o wa ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Obalende, ni o tumọ si ''ibi ti ọba le wa de" jẹ adugbo kan ti o wa ni aarin ilu Eko ni agbegbe ijọba ibilẹ Eti-Osa, ti o sunmọ Lagos Island..
wikipedia
yo
Eti-Osa yi ni ijoba Ipinle Eko pin si abẹ́ ijọba ibilẹ Onidagba-soke , eyi ti Ikoyi- Obalende wa ninu rẹ..
wikipedia
yo
Awọn bárékè ti ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ati bárékè ti àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà ni wọ́n wà lẹ́nu odi Obalende..
wikipedia
yo