cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nígbà tí ó wà ní London, ó kópa nínu ìdánwò Institute of Chartered Accountants, èyí sin fún ní ànfààní láti di akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé gíga náà lọ́dún 1964..
wikipedia
yo
Ní àkókò yìí, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Brighton, Sussex, bẹ́ẹ̀ náà, lọ́dún 1963 sí 1964, ó bá ilé-iṣẹ́ ìṣirò-owó ti Bradley, Lytton & Co, ṣiṣẹ́ ni Moorgate, ní London..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1964,ó padà sí Nàìjíríà, ó sìn ríṣẹ́ sí ilé-iṣé Panell Fitzpatrick & Co, Chartered Accountants..
wikipedia
yo
O dara pọ mo ile ifowosowopo National Bank of Nigeria lodun 1967, oun sin ni oni ṣírò-owo fun won nigba ogun abele Naijiria..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìgbìmọ̀ ilé-iṣẹ́ West African Pictures, Nigeria Spinning company, àti General Insurance..
wikipedia
yo
Ọdún 1971,ni ó kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ ní National Bank of Nigeria, tí ó sin bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àdáni ara rẹ̀..
wikipedia
yo
O da ile-ise Getidwell Nigeria Ltd sile ki o to da The Punch sile lodun 1976..
wikipedia
yo
Ó kú ní ilé-ìwòsàn The Princess Grace Hospital, London..
wikipedia
yo
Kí ó tó kú, ó ṣe Àkọsílẹ̀ ọ̀rọ̀ ìròyìn láti láti já fún ètò akọ̀ròyìn ẹgbẹ́ rẹ̀ kan, Pọ̀nùn Adamu, tí ó jẹ́ olórí àwọn olùdásílẹ̀ ìwé-ìròyìn ní Nàìjíríà, tí ìjọba fi sẹ́wọ̀n..
wikipedia
yo
O jẹ okan gboogi ninu awon abenuate lu isejoba Aare Shehu Shagari.O joye Àṣìpa Parakoyi ni iluIbadan ki o to ku.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ibadan Grammar School ni ó jẹ́ ile-ẹ̀kọ́ girama kan ti ó wà ni agbègbè mọ́lẹ̀te ni igboro ilú Ìbàdàn ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .Ìtàn bi won se da sílẹ̀wọn dá ile-eko yi sile ni ojo kokanlelogbon osu keta odun 1913..
wikipedia
yo
Ile-ẹkọ yi jẹ ọkan pataki ninu awọn ile-ẹkọ ti o laami-laaka ninu awọn ile-ẹkọ girama ti o wa ni ilu Ibadan...
wikipedia
yo
Lásìkò tí ètò ẹ̀kọ́ bá ń lọ lọ́wọ́, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn lámèyítọ́ láwùjọ ìbádá ni wọ́n ma ń rán àwọn ọmọ wọn lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ yí fún ètò ẹ̀kọ́ tó yanrantí..
wikipedia
yo
ní ọdún kẹtàlélãlógùọgbọ̀nọgbọ̀n àkọ́kọ́ tí wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀, àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ọkùnrin nìkan ni wọ́n ń gbà wọlé láti kẹ́kọ̀ọ́ níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ile-ẹkọ yi di ile-ẹkọ fun takọ-tabo ní ọdun 1941..
wikipedia
yo
Laarin odun 1950 si 1960, won bere si ni fun awon akekoo ni iwe-eri "Higher School Certificate"(HSC) nigba ti won ba pari eko iwe mefa..
wikipedia
yo
Oga agba ile-eko akoko ni Alexander Babatunde Akinyele.Àwọn akẹ́kòọ́ jade Loemike Adenushe RosijiMichael Lelewaatàbí Hamid Adise Ibru Ibru agagubo IileMichael Olatunji Onajídéàwọn itọkasiìtàkùn Val1913 inmentsments in Nigeriacational òdòdó established in 1913Schools in IbadanSecondary Schools in Oyo State of Ibadan..
wikipedia
yo
The Punch jẹ́ iwe ìròyìn ojoojúmọ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ó da ni oṣù kẹjọ ọjọ́ 8, ọdún 1970..
wikipedia
yo
Punch Nigeria Limited ti forúkọsílẹ̀ lábẹ òfin àwọn ilé-iṣẹ́ ti ọdún 1968 láti ṣe ìṣòwò títẹ̀jáde àwọn ìwé ìròyìn àti àwọn ìwé ìròyìn ìgbà kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ àpẹrẹ láti sọ fún, kọ́ ẹ̀kọ́ àti ṣe èrè àwọn ọmọ Nàìjíríà àti àgbáyé lápapọ̀.Ìtàn James Aboderin, oníṣirò-owó, àti Sam àmúkà, ònkọ̀wé àti olóòtú ní Daily Times ti Nigeria ni ó dá ìwé ìròyìn Punch sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ni osu kokanla odun 1976, odun die lehin títẹ̀jáde akoko ti ikede Sunday rẹ, awon mejeeji bere tite iwe iroyin ojoojumọ aami-iṣowo wọn..
wikipedia
yo
Àwọn àtẹ̀jáde méjèèjì ni a ṣe láti ṣe ojúrere sí ọ̀nà ìṣèlú ọ̀rẹ́ ọ̀rẹ́ sí ììjábọ̀ ìròyìn, àpapọ̀ àwọn àwòrán ti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ pẹ̀lú àwọn ìròyìn ìṣèlú lójoojúmọ́..
wikipedia
yo
Ìwé náà dúró fúnra rẹ̀ nípa lílọ sínú àwọn ọ̀ràn gbòòrò tí ó nífẹ̀ẹ́ sí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyàn..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, lakoko aṣálẹ̀ ti Orilẹ-ede keji, awọn ijade ti iṣelu ti ṣafihan awọn ija si awọn ero atilẹba rẹ ..
wikipedia
yo
Aboderin àti Amuka pínyà nítorí apákan àwọn ìjà òṣèlú
wikipedia
yo
Aboderin lẹ́hìn na gba àtìlẹyìn ti Ota rẹ tẹ́lẹ̀, MKO Abiola, lẹhin ti igbẹhin ti kuro ni NPN ..
wikipedia
yo
ìwé náà bẹ̀rẹ̀ sí mú ipò òṣèlú, púpọ̀ jùlọ lòdì sí ìjọba Shagari..
wikipedia
yo
A rò pé, àwọn ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú òpin ìṣàkóso ti Shagari, díẹ̀ nínú àwọn olóòtú Punch tí mo pè ìfipábánilòpọ̀ ń súnmọ́ àti fi àwọn ohun orin tí ó lòdì sí ìjọba tí ó lágbára nínú ìjábọ̀ wọn.Òmìnira tẹ Punch kò ní àjẹsára sí ìlòkulò tí àwọn ìjọba aláṣẹ ní orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1993 àti 1994, wọ́n ti ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé náà pa lórí ìdarí Alákòóso orílẹ̀-èdè náà.ilé-iṣẹ́ náà Punch Nigeria Limited ti forúkọsílẹ̀ ní Oṣù Kẹjọ ọjọ́ 8, Ọdún 1970, lábẹ́ òfin àwọn ilé-iṣẹ́ ti 1968 láti ṣe ìṣòwò títẹ̀jáde àwọn ìwé ìròyìn, àwọn àpapọ̀ àti àwọn ìwé ìròyìn ìgbàkọ́kọ̀ọ̀kan ti àwọn ànfàní ìlú..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ naa ni Igbimọ Awọn Oludari, Eyi ti o jẹ eto eto imulo ti o ga julọ ti Ile-iṣẹ naa.Ni ọdun 1971, Ile-iṣẹ naa ṣe iṣafihan akọkọ rẹ pẹlu títẹ̀jáde inu happy home, iwe irohin ti idile kan..
wikipedia
yo
Ni ojo Sunday, March 18, 1973, iwe iroyin akoko ni ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀, Sunday Punch, Kọlu ile itage..
wikipedia
yo
Àkòkòpọ̀ nípasẹ Ajibade fa-Thomas Punch, taBloid ojoojumọ ojoojumọ kan tẹ́lẹ̀ ní Oṣù kọkànlá Ojo 1, ọdún 1976..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, nipasẹ awọn ọdun 1980, a ti tunpo taBloid meji naa.Ni April 29, 1990, ọ̀sẹ̀ kan leyin igbiyanju ìdìtẹ̀ si ijoba apapo, won ti ile ise naa palẹ̀..
wikipedia
yo
Tiipa naa je osu kan lakoko ti Igbakeji olóòtú ti the Punch, Chris Mammah, ti wa ni Àtìmọ́lé fun ọjọ 54..
wikipedia
yo
lẹẹkansi ni Oṣu Keje ọdun 1993, Ijọba Ológun Federal ti tii Ile-iṣẹ ti Ile-iṣẹ naa, fi ofin de No 48 ti 1993, o si Fòfinde Gbogbo awọn atẹjade rẹ lati kaakiri ni Orilẹ-ede naa..
wikipedia
yo
Pípàdé naa tẹle Aáwọ̀ olu ti o fa nipasẹ ifagile ti June 12, 1993, idibo alakoso.Ni osu Kọkànlá ojo 17 ti odun kanna, ase aṣẹ-aṣẹ ti fagile ni iwe aṣẹ no 115 ti 1993..
wikipedia
yo
Ìjọba Ológun Federal kọlu ni Oṣu Keje ọjọ́ 24, ọdun 1994, wọ́n si fi ofin de gbogbo àwọn akọle pẹlu TopLife, eyi ti a ti sọji ti a si tẹ̀ jade bi iwe irohin osẹ kan lẹhinna..
wikipedia
yo
Olóòtú the Punch nígbà náà, Bola Bolawole, wà ní àtìmọ́lé ọjọ́ mẹ́ta ní ọ́fíìsì rẹ ní ilé àtijọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tíipa náà, ìjọba kọbi sí àṣẹ ti ilé-ẹjọ́ kan pé wọ́n gbọdọ̀ kúrò ní agbègbè ilẹ̀ náà àti tún san owó mílíọ̀nù 25 àti N100,000.00 fún ilé-iṣẹ́ náà àti Bolawole..
wikipedia
yo
Ní àkókò yẹn ó ní iyàrá tí ó pọ̀jù ti 12,000cph àti gígé-pípa 22.75ins tàbí 578mm..
wikipedia
yo
Ni àwọn ọdún àìpẹ́, imudara tí a ṣe sí agbègbè pẹ̀lú ìyára àti àwọn ìgbéga iṣẹ́ ṣíṣe àti àfikún àwòṣe ṣìpẹ̀Sifikesọnù gíga tí a pè ní Magnum..
wikipedia
yo
Punch te, ti o ni àwọn ìwọn àwo tí ó gbò, ní agbára láti tẹ̀ àwọn ojú-ìwé mẹ́jọ ti Àwo kíkún àti Àwo mẹ́jọ tí ó wà ní ojú-ìwé 48, àti pé ó máa ń lọ ní iha ì-oòrùn Nàìjíríà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ́ àwọn ìwé-ìròyìn tó gbajúmọ̀, tí wọ́n sìn kárí gbogbo orílẹ̀-èdè, tí wọ́n ń tẹ̀ jáde gẹ́gẹ́ bí ìwé àti àwọn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde lórí ìkànnì ayélujára ní Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Èyí ni àtòjọ àwọn oníròyìn (àhesọ) ìkànnì ayélujára tó gbajúmọ̀ jùlọ ní Nàìjíríà Alex NwankwoChude Jideonwọ̀de Greyjaphepheth J..
wikipedia
yo
Omojuwajutyl AuduKenneth Uwadif Omolọ́lù-NAPloyoKola TubosunLinda ikejiluvvie Ajayimyne Whic35noble IgweTolu OgunLesi AjibauwaCheche Yeseun Oobawa Jideonwowo Williams blogger Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìwé ìròyìn gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ní ìwé àtẹ̀jáde ọlọ́jọ́ojúmọ́ tí wọ́n fi ma ń kọ tàbí sọ nípa ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ lọ́wọ́ tàbí ohun tí ó ń lò nínú àwùjọ kan..
wikipedia
yo
Ìwé ìròyìn ma ń sábà sọ̀rọ̀ nípa oríṣiríṣi bí ọ̀rọ̀ ìṣèlú, okòwò, eré ìdárayá, iṣẹ́ ọnà, ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì, ọ̀rọ̀ nípa ojú ọjọ́, ìkéde ayẹyẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ó sì ma ń ní àlàfo tí àwọn ènìyàn lè fi sọ nípa bí ọ̀rọ̀ kan ṣe rí ní pàtó.Púpọ̀ nínú àwọn ìwé ìròyìn ni wọ́n sábà ma ń jẹ́ iṣẹ́ iṣẹ́ tàbí okòwò fún àwọn tí wọ́n bá dá irúfẹ́ ìwé ìròyìn bẹ́ẹ̀ sílẹ̀, wọ́n sábà ma ń fi ìwé ìròyìn pawọ́ nígbà tí àwọn ènìyàn bá polówó okòwò, ọjà, tàbí ayẹyẹ èyíkéyí tí wọ́n bá fẹ́ ṣe lórí ìwé ìròyìn kan..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, iwe iroyin kìí ṣe ọ̀fẹ́, bí kò ṣe tita fún ẹnikẹ́ni ti ó bá fẹ́ jànta ìròyìn nínú ìwé náà..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n gbé ìwé ìròyìn ọlọ́jọ́ojúmọ́ jáde ni a pè ní oníṣẹ́ ìròyìn tàbí oníròyìn ní ṣókí.Nígbà tí ìwé ìròyìn kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ń jáde láyé àtijọ́, orí ìwé fífẹ̀ fẹ̀rẹ̀gẹ̀dẹ̀ ni wọ́n ma ń kọ àwọn àkòrí ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí ó gbọ́mọ pọ́n Lorisrisi tí ó ń tọ́ka sí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ onírúurú tí ó ń lò láwùjọ sí..
wikipedia
yo
Pupọ àwọn ìwé ìròyìn ni wọ́n má ń kọ pẹlu òǹtẹ̀ aláwọ̀ dúdú ati funfun gbé jáde..
wikipedia
yo
Àmọ́ láyé òde òní, àwọn ìròyìn tàbí ìwé ìròyìn ni wọ́n ti ń gbé jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára fún ìrọ̀rùn àti rí ìròyìn kà níbikíbi àti ní ayékáàyẹ̀ lágbàáyé nípa lílo ìkànì tí yóò tọ́ka sí ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn kan tàbí òmíràn, fúndi èyí, púpọ̀ nínú àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn ni wọ́n ti pa kí wọ́n ma kọ ìròyìn sí orí ìwé fífẹ̀ fẹ̀rẹ̀gẹ̀dẹ̀ tí látàrí ìrọ̀rùn tí ìtàkùn ayélujára ti mú wá bá wọn.Ìwé ìròyìn ni wọ́n ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀ ní nkan bi ọ̀rúndún mẹ́tàdínlógún sẹ́yìn láti lè máa fi jáde ìròyìn nípa okòwò, àmọ́ nígbà tí yóò fi di nkan bí 19th Century, àwọn orílẹ̀-èdè bí Europe, North àti South Amẹ́ríkà bẹ̀rẹ̀ sí ní fi gbé àwọn ìròyìn jáde lórí oríṣiríṣi ohun tí ó ń lọ ní àwùjọ wọn gbogbo.ìwòye lórí ìwé ìròyìn wọ́n ma ń gbé ìwé ìròyìn jáde ní ojoojúmọ́, tàbí ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé ìròyìn alákànse tí a mọ̀ sí “Magazine” náà mà ń jẹ́ ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ bákan náà, àmọ́ ìrísí àkọsílẹ̀ wọn ma ń yàtọ̀ sí ti ìwé ìròyìn pọ́ńbélé.
wikipedia
yo
Lápapọ̀, gbogbo ohun tí ó bá ń lọ ní àwùjọ ni ó ma ń jẹyọ nínú àwọn ìwé ìròyìn ọlọ́jọ́ojúmọ́ àti ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n sì ma ń ṣe àgbékalẹ̀ ìròyìn náà gẹ́gẹ́ bí àyọkà sí ojú-ewé ìwé ìròyìn, àwọn ìròyìn bí ìròyìn tí ó ṣe pàtàkì, ìròyìn àgbáyé, tàbí ìròyìn nípa orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti ń tẹ ìwé ìròyìn náà ni wọ́n ma ń gbé sí àwọn ojú ìwé ìròyìn..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n tún ma ń fi ìwé ìròyìn ṣe eré ìdárayá ọpọlọ oríṣiríṣi..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú àwọn oniwe ìròyìn ni wón ma ń gba àwọn ámẹ̀ní bíi tiwọn ṣíṣẹ́ tí wón sì ma ń sanwó fún wọn, àwọn oniwe ìròyìn náà tún ma ń pawó wọlé sílé iṣẹ́ wọn pẹ̀lú kí wón ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ìlèṣẹ ìwé ìròyìn kéréje kéréje nípa fífún wọn ní àǹfàní láti lo ojú òpó wọn láti fi tẹ ìwé ìròyìn tàbí gbé ìròyìn tiwọn náà jáde..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ninú wọn naa si tún ma n gba àwọn oníròyìn bíi tiwọn lati kọ, tó, jábọ̀ rẹ, ti wọn yóò sì ta ìròyìn náà fún àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn míràn lati gbé jáde..
wikipedia
yo
the late 2000s-early 2010s global recharts, combined with the rapid growth of free web-based Dodves, has helped cause a decline in advertising and circulation, as many Papers had to reÈké operations to Stanch the Losses.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
strawberry Prince (Sutopu Sutopua) jẹ́ ẹgbẹ́ orin ọkùnrin Japan..
wikipedia
yo
Baptist Academy, jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama kan tí ó wà ní agbègbè Obanikoro ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Àwọn ajíyìnrere ará ilé Ametìka kan ni wọ́n wá dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ sí ìlú Èkó ní ọdún 1855..
wikipedia
yo
Ile-eko yi je eka ile-eko Reagan Memorial Baptist Girls' Secondary School, tí ó wà ní agbègbè Yaba ní ìpínlẹ̀ Èkó.ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹwọn dà ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn Ajiyin-rere tí wọ́n jẹ́ ọmọ Ooye-èdè Naijiria tí wọ́n ti ṣe àtìpó ní ilé Amẹ́ríkà dá ilé-ìjọsìn Onítẹ̀bọmi sílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó ..
wikipedia
yo
Ọba Ddaramu ti o jẹ ọba Eko nigba naa ni o fun wọn ni ile ti won fi kole ijosin wọn si..
wikipedia
yo
Láìpẹ́, ètò-ẹ̀kọ́ bẹ̀ẹ̀ẹ́ ní pẹrẹu, bí iṣẹ́ ìyìn-rere ṣe ń tẹ̀ síwájú náà ni ilé-ẹ̀kọ́ náà ń dàgbà sí..
wikipedia
yo
nígbà tí yóò fi di nkan bí ọdún 1888, ilé-ẹ̀kọ́ náà ti ní àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ọmọ ọkùnrin tí ó ti tó ọgbàọrùn un kan àti ẹyọ mọ́kàndínlógún, nígbà tí àwọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ obìnrin jẹ́ márùndínlo-ànọgọ́rùn ún, nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama jẹ́ mẹ́rìndínlógún lọ́kùnrin àti akẹ́kọ̀ọ́bìnrin mẹ́ta péré..
wikipedia
yo
Ṣáájú ọdún 1926, ajíyin-rere ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kan ni ó ṣe ọ̀gá àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ náà, àmọ́ ní inú oṣù kíní ọdún 1926, ọ̀gbẹ́ni ajíyin-rere ẹyọ ìta dara pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ náà gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ tí ó sì di ọ̀gá àgbà ilé-ẹ̀kọ́ náà..
wikipedia
yo
Ibi ti wọn kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ naa si tẹ́lẹ̀ ni àdúgbò Broad Street, ṣáájú ki wọ́n tó gbe lọ si ọ̀nà Ikorodu..
wikipedia
yo
Ile-eko alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nikan ni won kò gbé kúrò ní Broad Street, Sibe won yi oruko re padà sí W.J David Memorial Baptist Primary School nirántí olóògbé (William Joshua David) tí ó jẹ́ Ajiyin-rere ọmọ ilẹ̀ [[Amẹrika tí ó kọ́kọ́ gbé ìko Onítẹ̀bọmi wá sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ile-eko alakaleoobere yi wa ni Broad Street titi di ibere odun 1980 ki won to wo ile-eko naa lulẹ nigba ti won fe fa ile-ijosin eni ti o wa ni idakeji ile-eko naa siwaju si..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ilẹ̀-ẹ̀kọ alákadá ibẹ̀ ni wọ́n fi sọ̀kò sí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ àlàkalẹ̀ó kábẹ̀rẹ̀ Onítẹ̀bọmi tí ó wà ní agbègbè ibẹ̀.Ọ̀rọ̀ Akin-ẹ́kọ́ náà náà Duce which means God is my leader.Mana ilé-ẹ̀kọ náà baʹlógèdèbaba-6m ìṣe]. Wọn are baptist Academy boys andwe're proud of our dear Alma lojoojumọwhere sweet fellowship we all enjoywhere the spirit of Christ is taughtwhere our Captain, God, lead us alongwe"ll be true to our Alma mater Always.Up School up lati Totojo awon olukọ agbasome of the Principals of the school include Prof..
wikipedia
yo
Adegbitẹ(first Nigerian principal of the School) 1954 - 1975 Mr..
wikipedia
yo
Gbenga Abọ́dúnrin 2018 Kox dateàwọn akẹ́jade to ti laami-làádélé Mobọ́láji Bank Anthonyk.O..
wikipedia
yo
M̀bá-wẹ̀sì Chief kesogunogun Adebu Founder Premier Lotto (Baba Ijebu)Olu Ogunto former Sports Administrator, Former chairman of Lagos State Boxing Association, former so Administrator of Lagos State Sports Councilẹkùndayo Ọ̀pá former Military Governor Governor of Ondo State. Okoya-Thosola Onabanjo Gomina Gómìnà Akoko àkọ́kọ́ fun Governor of Ogun StateBabatunde Kwaku Adahhrátì AgeDAHDA Nigerian Lawyer and journalih Prata Orieri Notable playwright Wahab Dosunmu and Senator Ifa Gbemi FIV Fræls, Private Dete, Actible.Michael Gowole Bámidélé Nigerian Lawyer, Human Rights Activist, Member of 7th National 2016 Momoh CEO of Channels TV O- 2016-winning A Anahouse Fi Ana Vice Oyen of Lagos State AdeSamuel Akintola from teacher at Baptist at Kuti Nato musician A 2016 ↑ We We Bank We ìrẹ́pọ̀ chairman Great Al Insuta Great f[La Carto O 2017ce with 2017 to Education in 2016 List in Schools in LSTEN In Dd Apon - N ori Lagos ..ments in baptist Schools in Nigeria Best established in 1855 in 2015 in Lagos States in Lagos..
wikipedia
yo
Iwọ Xe (XX sheng You ) (ti a bi ni Oṣu Kẹwa Ọjọ 1, Ọdun 1958 ni Hajújú, China) jẹ oloselu ará ilu Jamani kan, oludije fun idibo ile Igbimọ Asofin European 2019, Oníṣẹ́ iroyin ati onkọwe abinibi Ilu Ṣáínà...
wikipedia
yo
Ọdún 2021 (ọdún ìga ó lé mọ́kànròyìn tàbí mmx ní ìka nọmba Romu) bẹrẹ ni ojo Ẹti ninu kànda GRegori.O le ka eleyi na 20222021..
wikipedia
yo
(tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlá Oṣù Kìíní Ọdún 1975) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anámbra lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Igba Ewe Adyl, jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Anámbra..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama kí ó tó kàwé gboyè ní University of Maiduguri, lápá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìànímọ́ sinimá àgbéléwò rẹ̀ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́ta lé ní igba (250)lára àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa ni; Power of Trust Scent of Passion Holy Cross The Shepherd the Genejúbà Power of Love Tears of the Blind Emotional Tears The Catta ọ̀gbanta The Family Hunter Poverty scent of Passion Runaway ẹ̀sìn Holy Cross retaliation Death of Shita Rambo the Family the Illiterate Days of My Wedding Wedding Pandemeric to Love an Angel different World Tears of the Blind Pans Indiad Agi Born to Sudddddd The Rerírán Mo Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ademola Adẹ́bise ni o je adari agba ati olootu agba yan yan fun ile-ifowopamọ Wema Bank Plc.Igba ewe rẹwọn bi Adebisi ni won bi ojo kokanlelogbon osu kẹwàá odun 1966 , ni ipinle Eko sinu ebi Ogbeni ati arabinrin Adegoke Adẹ́bise..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Baptist Academy tí ó wà ní ìlú Sùúrùlérè ní àárín ọdún 1972 sí ọdún 1978, tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ fìní Yunifásítì ti Èkó níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ Kọ̀pútá láàrin 1983 sí ọdún 1987..
wikipedia
yo
Adẹ́bi gba oye dìgírì Kejì nínú ìmọ̀ Business Administration (MBA) ní ilé-ẹ̀kọ́ Lagos Business School tí ó sí ilé-ẹ̀kọ́ Advanced Management Program (AMP) tí ó wà nínú ilé-ẹ̀kọ́ Harvard Business School.Iṣẹ́ readebise tí ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé isẹ́ Information Technology Company tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí programmer àti Alààyè ÌMỌ̀ MẸ́m̀já ní ọdún1988 láti ọdún ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣiṣẹ́ nílẹ̀ ìfowó-pamọ́ Stanọdún IBM ní ẹka eto ìmọ̀ ẹ..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ olókòwò bi Nigeria Inter-bank settlement system PLC (NIbSS), YCO Insurance PLC àti ÌCO PenSi Manader Limited’’àwọn ibi tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Institute of Chartered Accountants of Nigeria The Chartered Institute Institute of Taxation of Nigeria The Chartered Institute of Bankers of Nigeria The Institute of Directors of Nigeria the Computer Professionals (Regiclusi Council of Nigeria) Cineàwọn Àmì-ẹ̀yẹ Reper Day Day for the Top 25 Ceos in Nigeria (2009)ìgbé ayé readẹ́bise ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Arábìnrin AdeJùmọ̀kẹ́, wọ́n sì bimọ mẹ́ta.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1966àwọn Ọjọ́ìbí ní 1966àwọn ènìyàn Alààyè of Lagos alumni Business School Advanced Management program Valde Attoes, Chief executives bankers Bankers Academy (Pan-Atlantic University Ibi Lagos From Lagos-Century Nigerian Business-21st Century Nigerian Business..
wikipedia
yo
Olóyè ti orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ Sunday Adéniyi Adeyẹ (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1972 ) jẹ́ gbajúmọ̀ ajìjàǹgbara, olóṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ajìjàngbara fún ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè Oòduà àti ìṣọ̀kan àwọn ọmọ Yorùbá káàkiri Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni alaga ati oludasile Ile-iṣẹ Adeson International Business Concept Ltd, bẹẹ naa won fi oye akoni Oòduà Ilẹ̀ Yorùbá daa lola..
wikipedia
yo
Sunday di ìlúmọ̀ọ́ká lórí ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lóṣù kìíní ọdún 2021, nígbà tí ó fún àwọn darandaran Fúlàní ní gbèdéke ọjọ́ méje láti kúrò nílé Ìbàrà, nítorí ìpakúpa tí wọ́n fura pé àwọn Fúlàní wọ̀nyí ni ó pa ọ̀mọ̀wé àbọ̀ròde.Ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí Sunday ní ìlú ìgbhò, lókè-ogun ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bàbá re tọ́ ọ dàgbà ní ìlú mọdákẹkẹ ní ìpínlẹ̀ Osun..
wikipedia
yo
O kọ́ṣẹ́ mọṣẹ́ nipa tuntun kẹkẹ alùpùpù ṣe, eyi lo fi n jẹun ki o tó tun bẹ̀rẹ̀ tuntun ọkọ̀, lẹ́yìn èyí ló bẹ̀rẹ̀ sí ní ta ọkọ̀ ayọkẹlẹ ki o tó dá ilé-iṣẹ́ Adeson Business Concept sílẹ̀.O bẹ̀rẹ̀ sí ní di gbajumọ ìlúmọ̀ọ́ká nipa ipa akọni tí o kó nínú ogun Barkẹ́kẹ́ ati Ifẹ̀ láàarín ọdún 1997 sí 1998, nibi ti o ti gbe lẹ́yìn àwọn ènìyàn Barkẹ́kẹ́..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó pada sí Ìbàdàn, níbẹ̀ lọ ti pàdé gomina ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àná, Lam Adéṣínà nípa ìgbésẹ̀ akin tí ó gbé nílé epo kan láti gbèjà ati jà fún ẹ̀tọ́ àwọn eniyan níbẹ̀..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó bá gómìnà àná ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ mìíràn, Rashheed Ládọjà ṣiṣẹ́, tí ó sìn di ọ̀kan nínú àwọn ìsọ̀ǹgbè olùfọkàntán rẹ̀.Gẹ́gẹ́ bí akọni ilẹ̀ OòduàSunday gbajúmọ̀ nípa jíjà fún ètò Yorùbá nípa lílo oògùn àti agbára ìbílẹ̀ bákan náà ni ó ń sapá àti akitiyan láti lè jẹ́ kí àwọn ọmọ Yorùbá ó dá dúró gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè Olómìnira lábẹ́ orúkọ “orílẹ̀-èdè Oòduà...
wikipedia
yo
Ni Oṣu Kẹwa ọdun 2023, Sunday Igboho ti tu silẹ ni Ilu Benin nibiti wọn ti mu u lẹhin ti o salọ fun ọlọpa ni Nigeria ni ọdun 2021..Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka Iná ni Nigeria n gbejade, tàn káàkiri àti pínpín àwọn megaWatts ti agbára iná eléyí tí ó dínkù ní pàtàkì ju ohun tí ó nílò láti pàdé àwọn ìpìlẹ̀ ilé àti àwọn àìní ilé-iṣẹ́..
wikipedia
yo
ní ọdún 2012, Ilé-iṣẹ́ ṣíṣe láti pín àwọn megawátt 5,000, púpọ̀ tí ó kéré sí 40,000 megaSOAN tí ó nílò láti ṣe àtìlẹ́yìn àwọn àìní ìpìlẹ̀ ti olùgbé..
wikipedia
yo
àìpẹ́ yìí tún burú sí nípasẹ̀ fífúyẹ́ fífisílẹ̀ tí a kọ́ kéde, apá kan àti lápapọ̀ ìṣubú ẹ̀tọ́ àti ìkùnà agbára..
wikipedia
yo
Láti pàdé ìbéèré, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé àti àwọn ilé-iṣẹ́ lómọ̀ sí rira àwọn ìrun ina lati fi agbára fún àwọn ohun-ini wọn, orisun orí agbára yìí ti pese 6,000 mega ní ọdún 2008.Ìtàn-akọ idagbasoke ilé-iṣẹ́ agbára òina ina ina ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ ní ìlú [[Èkó]] ní ọdún 1886 pẹ̀lú lílò àwọn èro ina lati pese kilo 60.. 60..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1923 awon ti n wa ni tin fi sori ero ogbin 2 MW lori Odò Kwali, ni odun mefa lẹhinna, Ile-iṣẹ ìpẹ̀sẹ̀ ina ìtànná Naijiria, Ile-iṣẹ Aladani kan ti mulẹ nitosi Jos lati ṣakoso ogbin Hyd-ẹ̀léc ni kúrá lati fi agbara fun Ile-iṣẹ ìwakùsà..
wikipedia
yo
Lẹhinna ile-iṣẹ aladani miiran ni a ṣeto ni Sapele nipasẹ ile-iṣẹ Amerika Afirika lati fi agbara fun awọn iṣẹ ti African Tija ati ile-iṣẹ plywood..
wikipedia
yo
Laarin ọdun 1886 si 1945, iran agbara ina kuku dinku pẹlu agbara ti a pese ni pataki si Eko ati awọn ile-iṣẹ iṣowo miiran gẹgẹbi awọn ile-iṣẹ ìwakùsà ni Jos ati Enugu..
wikipedia
yo
Ijoba amunisin ṣẹda eka ina kan laarin ẹka awọn iṣẹ gbogbogbo eyiti lẹhinna fi sori ẹrọ awọn ipilẹṣẹ ina ni ọpọlọpọ awọn ilu lati sin awọn agbegbe ifiṣura ijọba ati awọn ile-iṣẹ iṣowo..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1950, Igbimọ-Ofin ti Nigeria bẹrẹ gbigbe lati sepo Ile-iṣẹ ina nigbati o ṣe agbekalẹ ofin lati fi idi ile-iṣẹ itanna ti Nigeria mulẹ pẹlu awọn iṣẹ ṣiṣe idagbasoke ati fifi ipese ina..
wikipedia
yo
EC gba awon ise aladani ina laarin pjìyàjìyà ati awon ipilẹṣẹ ipilẹṣẹ ti awon alaṣẹ ilu abinibi..
wikipedia
yo