cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àpapọ̀ iye àwọn eniyan tí wọ́n ní àrùn náà ń pọ̀ sí lọ́jọ̀óo ó gba ilẹ̀ Afirika ní ọjọ́ méjìdínlọ́gọ́rùn-ún (98)láti kéde ẹni ẹgbẹrun lọ́nà ọgọrun-un tí wọ́n ti kó àrùn náà, lẹ́yìn náà, ó gba Afirika ní ọjọ́ mejidinlogun péré mìíràn láti kéde àwọn eniyan mìíràn tó tó ẹgbẹrun lọ́nà ọgọrun-un mìíràn..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ ni iye àwọn eniyan tí wọ́n kó àrùn náà ń pọ̀ sí, bí ó ti gba ilẹ̀ adúláwọ̀ ní ọjọ́ méjìdínlọ́gọ́rùn-ún péré láti kéde eniyan ẹgbẹrun lọ́nà ọgọrun-un àkọ́kọ́ tí wọ́n kó àrùn náà, tí ó sìn jẹ́ pé ọjọ́ mejidinlogun péré mìíràn láti kéde owó keji ẹgbẹrun lọ́nà ọgọrun-un àwọn eniyan mìíràn tí wọ́n kó àrùn náà..
wikipedia
yo
Iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ń kó àrùn náà ń pọ̀ sì tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tó fi jẹ́ pé àpapọ̀ iye tí wọ́n ní àrùn náà pọ̀ tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún (300,000) àti ẹgbẹ̀rún lọ́nà irínwó (400,000) ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà..
wikipedia
yo
Ni ojo kejo osu keje, apapo iye awon eniyan ti won ti ni arun COVID-19 ni Afirika ti koja idaji Milionu kan lọ..
wikipedia
yo
Lóṣù kẹfà ọdún 2020, ìròyìn sọ pé, ó ṣeé ṣe kí Áfíríkà jẹ́ ibi tí àrùn COVID-19 yóò ti máa jàkalẹ̀ jùlọ ní àgbáyé, ti ìdajì àbọ̀ mílíọ̀nù àwọn tí wọ́n ní í wá láti South Africa àti Egypt..
wikipedia
yo
Hakeem Sekou Jeffries (; Ọjọ́ìbí August 4, 1970) ni oloselu ati Agbẹnu ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ Díalyan bíi aṣojú ilẹ̀ Àwọn aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà fún Ìpínlẹ̀ New York lati ọdún 2013..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ara ẹgbẹ́ DemoKratíkì.àwọn ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ara Américowọn ọmọ ilé aṣojú U.S..
wikipedia
yo
Ile awon asoju orile-ede Amerika (the United States House of Representatives ni ede Geesi) ni ilé aṣòfin kékeré ni Kongẹ̀sì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà; ilé àwọn alàgbà ní ilé aṣòfin àgbà..
wikipedia
yo
Lapópó awon mejeeji je ile-aṣofin onileIgbimọ-meji (Bicameral legislature) fun orile-ede Amerika.itọkasi Amerika..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè Mali ní Oṣù Kẹta ọdún 2020.Ìpínlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù ìkíni ọdún 2020, àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn erankorona ni ó fa àrùn atégùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìlú Wuhan, agbègbè Hube ní orílẹ̀-èdè China èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 kéré púpọ̀ sí ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkájì àrùn ti SARS tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2003 ṣùgbọ́n bí àrùn yí ṣe ń tàn káká kiri pọ̀ púpọ̀ ní pàtàkì tí a bá wo iye àwọn tí ó ti jẹ́ aláìsí.àwọn àkókò tí àrùn yí ń tàn àti àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí ó ń ṣẹlẹ̀ oṣù ọdún 2020 ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, orílẹ̀-èdè Málì fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn àrùn COVID-19 méjì àkọ́kọ́ múlẹ̀.Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ilé-iṣẹ́ tí ìlera àti àwùjọ ṣe Àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun méjì..
wikipedia
yo
Ni erongba ati dojuko ajakale-arun ti o n ja orile-ede yi, Aare orile-ede olominira ti Mali, Ibrahim Boubacar keta, kede ipo pajawiri ni ilu ati ofin kónílé o gbele lati agogo mesan an aṣalẹ si agogo marun un owuro ninu oro re si awon omo orile-ede Mali..
wikipedia
yo
Ni ojo ketadinlogbon osu keta, pelu ayewo tuntun meje ti o fidi erankorona mule ni Mali, isele erankorona ni orile-ede Mali lo soke si isele mokanla.Ni ojo kejidinlogbon osu keta, won fidi isele tuntun meje mule, apapo iye awon ti won ti ni arun COVID-19 wa di mejidinlogun..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ ẹni àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ aláìsí látipasẹ̀ àjàkáta-àrùn COVID-19 ni ó wáyé ní Oṣù yí.Ní Ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ènìyàn márùndínlọ́gbọ̀n ní àyẹ̀wò fìdí rẹ múlẹ̀ pé wọ́n ní àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19..
wikipedia
yo
Awon ti n se akoso eto ilera so wipe awon eniyan meji lo je alaisi.osu kerin odun 2020 ni ipari osu kerin, isele 490 ni won fidi re mule ninu eyi ti awon eniyan 329 n se aisan lowolowo ti awon eniyan merindinlogbon si ti je alaisi.osu karun un odun 2020 ni ipari osu karun un, isele 1265 ni won fidi re mule ninu eyi ti awon eniyan 472 n se aisan lowolowo ti awon eniyan apere ti je alaisi.osu kefa odun 2020 ni ipari osu kefa, isele 2181 ni won fidi re mule ninu eyi ti awon eniyan kini n se aisan lowolowo ti awon eniyan 116 ti je alaisi.osu keje odun 2020 ni osu keje, isele 354 ni won fidi re mule, eyi ti o mu ki apapo gbogbo isele arun korona ni orile-ede Mali di 2,535 ninu eyi ti awon eniyan 474 ti won n se aisan lowolowo ni opin osu keje..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti je alaisi lo soke lati mejo si mẹ́rìnlélọ́gọ́fà(124).osu kejo odun 2020 lati ojo kini osu kejo si ojo kerindinlogun osu kejo,eyi ti i se ojo meji saaju ìṣọ̀tẹ̀ ti o yori si eyi ti awon ologun fi gba ijoba ni orile-ede yi, isele 2,640 ni won fidi re mule..
wikipedia
yo
Awon alaisan 528 ni won n gba itoju lowolowo nigbati awon 1,987 alaisan ti ri iwosan gba ti awon alaisan ti o ti ku je marundọmọ(125)..
wikipedia
yo
Ni oṣù kẹjọ yi, àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ òjìlénígba lè kan(241) ni wọ́n tún súyọ èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn yí di 2,776..
wikipedia
yo
Iye àwọn aláìsàn tí ó kú lọ sókè sí mẹrinọ̀wọ́(126)..
wikipedia
yo
Ni opin osu yi, awon ti o n gba itoju lowolowo je 48.OsunOsun kesan an odun 2020 titi di ojo kejila osu kesan an, 2,916 ni iye awon isele ti won fidi re mule , ninu eyi ti o je wipe awon ti o n gba itoju lowolowo je apolonia, awon alaisan ti o ti ri iwosan gba je 2,276 nigba ti awon alaisan ti o ti ku je mejidinlaadoje(8080)..
wikipedia
yo
Ninu awọn ojo ti o seku ninu osu kesan an, awon isele marunidìrage(185) miran ni o tun súyọ eyi ti o mu ki apapo iye awon isele arun korona di 3,101 ni orile-ede Mali..
wikipedia
yo
Àwọn mẹta tí ó tún jẹ́ aláìsí mú kí àpapọ̀ iye àwọn tí ó ti kú di mọ́kànléláà131)..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan lo soke si 2,443 eyi ti o wa mu ki iye awon alaisan ti o n gba itoju lowolowo je 527 ni opin osu kesan an.Awon ona lati dena arun COVID-19 ni ojo kejidinlogun osu keta, Aare Ibrahim Boubacar keita da awon oko ofurufu ti won n bo lati orile-ede ti ajakale arun yi ti n sele duro..
wikipedia
yo
Ààrẹ tún ti àwọn ilé-ẹ̀kọ́ pa, ó sì fagilé àwọn àpéjọ tí ó bá tóbi..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, àwọn idibo ti wọn ti gbero pe yi o waye ni Oṣu Kẹta si osu kerin, eyi ti won ti n sun siwaju ni ọpọlọpọ igba tẹlẹ nitori pe ipo ti eto aabo wa ni orile-ede ko dara, ni wọn te siwaju lati se gege bi won ti gbero re.Ìtọ́kasí Malimali..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl is je ọ̀kan lára ìbúrẹ́kẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn korona tí a tún mọ̀ sí KOFId-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
ohun tí ó ń ṣokùnfà àìsàn yí ni àrùn ọ̀fun, àyà, ati imú tí wọn ń pè ní severe ACUte àsárópirátory syndrome coronavirus 2 ()..
wikipedia
yo
Wọ́n fìdí ìwọlé sí orílẹ̀-èdè Sẹ̀nẹ̀gàl ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
Bi o ṣe bẹrẹ ajo isokan ti o n ri si ilera ni agbaye fidi arun korona ti a tun n pe ni Kofid-19 ni orile-ede agbaye ni ojo kejila osu kinni ni odun 2020..
wikipedia
yo
Tí wọ́n sì fìdí rẹ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tó ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé létí.Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ síwájú sí wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, òun ni ó ń fa ìfunpínpín ní ní inú káà ọ̀fun àti àyà, tí ó sì ma ń fa kátà tàbí kí ènìyàn ó má wú ikọ̀ tàbí sìn léra léra..
wikipedia
yo
Iye ijamba ti arun korona ti fa lagbaye kere si iye ijamba ti aisan arun ọ̀fun SARS ti fa lati ọdún 2003..
wikipedia
yo
Amo iye awon eniyan ti won to arun korona latari rírán ti o.n ran kale ti.Po ju ti SARS lo.,awon asiko kookan ti o sele ni ojo keji osu keta odun 2020..
wikipedia
yo
Arákùnrin kan tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnléláàádọ́ta tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Faransé ní ẹni àkọ́kọ́ tí ó kó àrùn [[COVID-19 náà wọ orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl..
wikipedia
yo
Arákùnrin yĩ ni ó n gbé ní agbègbè Álmàdies Arrondissement ní ìlúDakar, nígbà tí wọ́n ṣe àyẹ̀wò fún ní Pasteur Institute ní ìlú Dakar, ni wọ́n tó ri wípé ó ní àrùn korona..
wikipedia
yo
amọ̀ ṣáájú kí wọ́n tó ṣàyẹ̀wò fún ni ó ti kọ́kọ́ ṣe ìrìn-àjò tí ó sì wọ ọkọ̀ òfúrufú Air Senegal ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 2020..
wikipedia
yo
Bayi ni orile-ede Senegal di orile-ede kejiti yoo ni akosile arun àkóràn korona ni ile ìyàngbẹ Adulawo, leyin orile-ede Naijiria.akosile arun korona elekeji ni ti akosemose kan ti owa si Dakar lati ilu Faranse.Nigba ti yoo fi di ojo kerin osu keta odun 2020, iye awon eniyan ti o ti ni arun korona ti pe merin, ti gbogbo awon mẹ́rẹ̀rin si je àjòjì..
wikipedia
yo
Eni ti o je eni keta ti o ni arun yi ni iyawo eni akoko ti o koko ko arun naa wọ orile-ede Senegal, oun ni o de si iluDakar ni ojo kokandinlogun osu keta, nigba ti omo ile Britain kan ti o wa lati ilun lọdọn orile-ede Senegal ni ojo kẹrinlelogun osu keji.. odun 2020..
wikipedia
yo
Àwọn àjọ tí ó rí sí bọ́ọ̀lù aláfọwọ́-gbà , ìyẹn Basketball Africa League fagilé eré ìdíje ìbẹ̀rẹ̀ ọdún ní ọjọ́ kẹfà Oṣù Kẹta ọdún 2020, tí ó yẹ kó wáyé ní ìlú Dakar..
wikipedia
yo
èyí wáyé látàrí ìbẹ̀rù tí ó múlẹ̀ ṣinṣin tí àrùn náà ti dá sílẹ̀, tí ó sì mú kí àwọn ènìyàn ó má lè kóra jọ pọ̀ mọ́ nínú ilé ìjọsìn, ayẹyẹ pàá pàá jùlọ ayẹyẹ Grand Magal, tí ó níṣẹ́ pẹ̀lú ọdún Mouride tí ó ma ń wáyé ní touba tàbí ìrìnà-àjò káàkiri orílẹ̀-èdè Senegal, àti gbogbo àgbáyéní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta, Mínísítà fún ètò ìlera ọ̀gbẹ́ni abdoulaye Diouf Sarr, fi tó àwọn oníròyìn létí wípé ìjọba orílẹ̀-èdè Senegal yóò fòfin de ìpéjọọ́ tí ó jọ mọ́ ti ẹ̀sìn ìyẹn bí àwọn ará-ìlú bá fọwọ́ sí..
wikipedia
yo
Ni ojo ti Minisita fun eto ilera soro yi naa ni won tun fidi arun yi mule lara ikan ninu omo orile-ede Senegal ti o sese de lati orile-ede Italy, eyi si mu ki iye alaisan o goke si maruun gegbé.Ni ojo kejila osu keta, ijoba orile-ede Senegal tun kede akosile arun korona maruun míìra lara awon eniyan marun ọtọtọ, ti won je ebi alaisan karùún ti o de lati orile-ede Italy okan lara ninu awon ebi maruun ti won fara káṣà arun ni o wa ni ile mimọ ti touba, bi o tile je wipe awon olori elesin ni touba ti dànù wipe àrùnkárùn ko le mu enikeni ti o ba wa ni ilu touba naa.Nigba ti yoo fi di ojo kẹẹ̀ẹ́dógún osu keta, iye awon eniyan ti o ti ni arun korona ti to merinlelogun..
wikipedia
yo
Ijoba orile-ede Senegal duro de lilo-bíbò awon eniyan , won ti gbog o ile-eko pa fun ose meta, won tun duro fagile ìpéjọ-po ti o nise pelu esin eyikeyi léte ati dẹkun itankale arun COVID-19..Ni ojo Kọkànlá osu Karùún odun 2020, orile-ede senegal ti ni akosile ti o ti to ida ogbon..
wikipedia
yo
wọ́n sì sì gbẹ́sẹ̀ kúrò lórí òfin málò màbo, wọ́n tu ní kí gbogbo ilé-ìjọsìn ó padà sẹ́nu ìsìn wọn ní 9jo Kejìlá oṣù karùún..
wikipedia
yo
Iye ènìyàn tí ó ti kó àrùn COVID-19 ní àpapọ̀ jẹ́ 1,886, nígbà tí àwọn Gudún pàdánù ẹ̀mí wọn sí ọwọ́ àrùn korona.Ìdánĩ nípa àrùn Kabe orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gàl, púpọ̀ nínu àwọn ayàwòrán ni wọ́n fi àwòrán yíyà ṣe ìdánile àti ikilọ fún àwọn ènìyàn nípa bí wọ́n ṣe lè dẹ́kun àrùn korona tí ó ń ran kiri.Ẹ tún lè wò COVID-19 tòótọ́ in Africa COVID-19 Alv by Country and territory2020 in SenegalHIV/AIDS in Africawestern African Ebola virus Epidemic1918 Spanish flu Alv1957-1958 Influenza Panṣíríàpilẹ̀kọ nípa àrùn Conya Leveau Macọ̀wọ́ el, A., 2020..
wikipedia
yo
Festus 'Adegboye' Onigbinde (ọjọ́ìbí 5 osu keta, 1938 ni mọdákẹkẹ) ni olukọ bọọlu-afẹsẹgba ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ó ṣe olùkọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà ní ibi ìdíje ìfẹ́-ẹ̀yẹ àgbáyé FIFA 2002, kò tó di ìgbà yìí, ó tún ti jẹ́ olùkọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà lága ọdún 1982 àti 1984..
wikipedia
yo
Ni 1984, Onigbinde mu Naijiria de opin idije Ife-eye awon orile-ede Afrika ọdun 1984..
wikipedia
yo
Nàìjíríà kùnà lówó Kamerun pẹ̀lú góòlù 1–3 nínú ayọ̀ náà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ní ọdún 1984, ó di olùkọ́ fún 5ting Stars Sports Club ní Ìbàdàn, ó sì mú kúlòbu náà dé òpin ìdíje ìfẹ́-ẹ̀yẹ Africa Club Champions..
wikipedia
yo
Won kuna ayo opin lowo Zamale lati Egypt.Awon itọkasiawon oluko-afẹsẹgba araNaijiria araNaijiria..
wikipedia
yo
Karl Anthony Malone (ojoibi 24 Oṣù Keje, 1963) ní oníṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà tó ti fẹ̀yìntì..
wikipedia
yo
Wọ́n mọ́ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ "the Mailman", ó gba ipò Power Forward..
wikipedia
yo
O gba bọọlu fun ẹgbẹ agbabọọlu National Basketball Association (NBA) pẹlu Utah Jazz ati Los Angeles Lakers.Ìtọ́kasíàwọn agbabọọlu alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹrika..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Burundi àrù korona wọ orílẹ̀-èdè Burundi ní ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹrin ọdún 2020.Bi ó ṣe bẹ̀rẹ̀ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kíní Ọdún 2020, àjọ ìtara tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní Tod-19 ní orílẹ̀-M Àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó.ń ran kalẹ̀ tí.pọ̀ ju ti SARS lọ, * bí ó ti lè jẹ́ wípé itankale àrùn COVID-19 ń gbópọn sí lójojúmọ́ tí ó sì ti seku pa opol9po eniyan lagbaye..
wikipedia
yo
.Bí ó ṣe bẽrè ní àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kanoṣù kẹta ọdún 2020Mínísítà fún ètò Ìlera fún Orílẹ̀-èdè Burundi, ọ̀gbẹ́ni Tdèé ndikumana fìdí bí àrùn korona ṣe wọ orílẹ̀-èdè náà látara àwọn ènìyàn méjì kan wọ́n jẹ́.Ọmọ.Orílẹ̀-èdè Burundi tí wọ́n ń darí bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Rwanda àti ìlú àṣàùn..
wikipedia
yo
ní ọjọ́ ketàlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2020.Oṣù kẹrin ọdún 2020ni ọjọ́ kejì oṣù kẹrin, wọ́n tún fìdí àìsàn yí múlẹ̀ lára àwọn ènìyàn bí obìnrin ti ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju mẹrindílọ́gbọ̀n lọ, nígbà tí àwọn ènìyàn méjìlélógún tókù kò ní àrùn yí lẹ́yìn àyẹ̀wò àìsàn àrùn korona..
wikipedia
yo
Lapapọ, iye awon ti won tun ni arun yi ni aarin osu kerin n lo bi metala, ti o si mu ki iye awon alaisan korona je merindinlogbon..
wikipedia
yo
Ẹnìkan ṣoṣo ni ó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ sínú àìsàn náà ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin,àwọn mẹ́jọ ní ìmúlára dá rí ó sì mú kí ó jẹ.wípé.Àwọn àwọn mẹ́fà péré ló sì ní àrùn yí ní ìparí oṣù náà.Oṣù karùún ọdún 2020ní ọjọ́ Kejìlá oṣù karùún, aṣojú ilẹ̀ Burundi kọ ìwé kan sí ilé iṣẹ́ Àjọ Ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ọmọnìyàn lágbàáyé tí ẹ̀ka rẹ̀ tó wà ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, tí ó sì pàṣẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ mẹ́rin ilé-iṣẹ́ ètò ìlera náà tí ó ń ṣagbátẹrù ìdáhùn sí èsì áruw korona ní orílẹ̀-èdè Burundi wípé.Kí wọ́n palẹ̀ ẹrù wọ́n mọ́, kí wọ́n sì kúrò ní orílẹ̀-èdè.wọn kía..
wikipedia
yo
Iwe ti Aṣoju Orilẹ-ede Burundi naa ko sọ wipe awon oṣiṣẹ naa ti kọlu ofin ti wọn pe ni persona Non Grata , ti o tumọ si wipe won ko ni aṣẹ kan kan bi o ti wu ki o ri lati wọ orilẹ-ede.Burundi wa tabi ki wọn pe kọja gbèdéke ti ijọba ba fun wọn lọ..
wikipedia
yo
Fún èyí, wọ́n g odò kúrò ní orílẹ̀-èdè àwọn kí mẹ́ta ó tó pẹ́..
wikipedia
yo
Bákan náà, mínísítà tí ó rí sí ètò ìlera ní orílẹ̀-èdè Burundi náà.Tún fi ẹ̀sùn kan ilé-iṣẹ́ Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé tí ó rí sí ètò ìlera wípé wọ́n ń dá.Sí ọ̀rọ̀ ètò ìlera orílẹ̀-èdè àwọn ju bí ó ti yé lọ nípa bí àwọn ṣe ń mójú tó àjàkálẹ̀ àrùn korona.Nínú oṣù yí kan náà, wọ́n tún ní àkọsílẹ̀ ènìyàn tí iye wọn tó mejidinlaadọta tí wọ́n ti ní àrùn COVID-19, tí ó sì mú kí ìyá àwọn tí wọ́n ti ní àrùn yí ó fò fẹ́rẹ́ lọ sí mẹ́tàlélọ́gọ́ta, àmọ́ tí wọn kò pàdánù ẹ̀mí kọ̣́kan yàtọ̀ sí àwọn ti tẹ̀.Oṣù kẹfà ọdún 2020ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà, Ààrẹ ilẹ̀ Burundi Ọ̀gbẹ́ni Pierre Nkurunziza ṣe aláìsí látàrí àìsàn aya jíjà tí ó ma ń wáyé látara ẹ̀jẹ̀ ríru, gẹ́gẹ́ bí àwọn olóòtú ìjọba wọn ti sọ..
wikipedia
yo
Amo sa, awon ara ilu n fẹ̀ṣùn kan awon olootu ijoba wonyi wipe won ko sòtítọ́ nipa bi ajakale arun naa se n lo si ni orile-ede won, nitori wipe won gbe iyawo Aare won lo si olu-ilu Kenya fun itoju latari bi o se ni arun korona ni ojo mewaa saaju ikuoko ee..
wikipedia
yo
Some have speculated that the president died of COVID-19.Ninu osu karùún, iye awon ti won ti ni arun korona ti keke si 170, nigba ti won tun ni akosile iye awon eniyan ti o to ọgọ́rùún kan ati ẹyọ meje..
wikipedia
yo
Àmọ́ ẹnikọ̀kan kò kú, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n ti rí ìwòsàn lápapọ̀ ti fi ọgọ́rùún kan àti ẹyọ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún..
wikipedia
yo
gba iwosan.Àwọn igbese ìdènà arun korona ti won gbeìjọba orile-ede Burundi bere iyasoto ojo merinla gbáko fun awon eniyan ti won ba wo orile-ede naa wa lati awon orile-ede miran ti arun yi ba ti tan de soto si iyara adárin ni ojo kejila osu keta odun 2020..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, Ààrẹ ilẹ̀.Burundi ọ̀gbẹ́ni Nkurunziza kọ̀ jálẹ̀ láti fagilé ìgbòkè-gbodò àti lílọ-bíbọ̀ Àwọn ènìyàn ní orílẹ̀-èdè rẹ̀, nígbà tí ó sì fi àyé gba ìpolongo àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú àti eré ìdárayá lápapọ̀.Ẹ tún le wo COVID-19 tòótọ́ in Africa COVID-19 0 by Country and Territoryàwọn ìtọ́kasíBurundiBurundi..
wikipedia
yo
Wọ́n kéde àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní àwọn erékùṣù Kanari lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdún 2020, nígbà tí àyẹ̀wò arìnrìn-àjò kan láti orílẹ̀-èdè Jermánì fihàn pé ó ní àrùn náà ní ìlú là Gomera..
wikipedia
yo
Àdàyàn tí ó tún ní àrùn náà ní erékùṣù náà ni wọ́n kéde lọ́pọ̀ kẹrinleloguǹ Oṣù kejì ọdún 2020, lẹ́yìn tí wọ́n kéde òajakalẹ̀ àrùn náà ní orílẹ̀-èdè Italy, ní máa ńwo Dokita Dokita elé kan lati lombardy, ní Italy, tí ó wà lo isinmi ní ṣàṣàṣà yàn pé ó ní àrùn COVID-19..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní àwọn tí wọ́n ti ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú dókítà náà tún lùgbàdì àrùn náà ní Tenerife.Àkọsílẹ̀ àkọsílẹ̀ òòjọ́ ti ìjọba orílẹ̀-èdè náà ìkéde pé wọ́n ní àrùn COVID-19 ní àwọn Erékùṣù Canary.Ẹ yéyí wo àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin Aṣọ-iboju nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn Kariaye erankorona ọdún 2019 Àìsàn inú afẹ́fẹ́àwọn Ìtọ́kasí-19-19 Erékùṣù Kanari..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 bẹ́ sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè Central African Republic lóṣù kẹta ọdún 2020bi ó ṣe ìbẹ̀rẹ̀ kejìlá Oṣù Kìíní ọdún 2020 ní Àjọ elétò ìlera Àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé erankorona, COVID-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàarín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ Who lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019.Iye ìjàmbá ikú àrùn COVID-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severe ACUte Adcars syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún níbi, ṣùgbọ́n jíjákalẹ̀ àrùn náà lágbára jù SARS lọ, pàápàá jù lọ Iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀..
wikipedia
yo
Ero amúnimi meta pere ni o wa ni gbogbo orile-ede naa.jijakale arun naa lati igba de igbaosu keta odun 2020lọjọ́ kerinla osu keta odun 2020 ni won koko kede eni akoko ti o ni arun naa lorilẹ ede Central African Republic..
wikipedia
yo
Alárùn náà jẹ́ ọmọ ọdún onírùnlẹ ((74) ọmọ orílẹ̀-èdè Italy tó padà sí Central African Republic láti ìlú Milan.Ènìyàn mẹ́fà péré ni wọ́n kéde pé wọ́n ní àrùn náà lóṣù kẹta, kò sí ẹni tí ara rẹ̀ yá tàbí kú nínú wọn.Oṣù kẹrin ọdún 2020ènìyàn tuntun mẹ́rìnlélógójì ni wọ́n kéde wọ́n pé wọ́n kó àrùn náà..
wikipedia
yo
Èyí wá jẹ́ kí àpapọ̀ àwọn tí wọ́n ní àrùn náà di aadọta (50)..
wikipedia
yo
Ẹni mẹ́wàá rí ìwòsàn, tí àwọn ogójì sì ní àìsàn náà títí di ìparí oṣù náà.Oṣù karùn-ún ọdún 2020lọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún ni ẹni àkọ́kọ́ kú lórílẹ̀-èdè náà látàrí àrùn náà.Lóṣù karùn-ún, àpapọ̀ àwọn ènìyàn tuntun tí wọ́n ní àrùn náà jẹ́ olóòótọ́, èyí tí ó mú kí iye àpapọ̀ àwọn tí wọ́n ní àrùn náà ní Central African Republic jẹ́ ẹgbẹ̀rúnkanlẹ́mọ́kànlá (10–)..
wikipedia
yo
Eniyan meji pere lo ku, ti apapo awon ti won lu aluyo ninu aisan naa je metalelogun (23).osu kefa odun 2020lóṣù kefa odun 2020, iye awon eniyan tuntun ti won ni arun COVID-19 lórílẹ̀-ede Central African Republic je 2734, eyi je ki apapo awon ti won ni arun naa nibe je 3745..
wikipedia
yo
Àpapọ̀ àwọn tí àìsàn náà pa jẹ́ mẹ́tadikùn (47)..
wikipedia
yo
Iye awon ti won ri iwosan gba je 878,ti apapo iye awon ti won si ni arun naa je 2911 titi di ipari osu naa.Awon itọkasiCOVID-19..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè Mauritania ní oṣù kẹta ọdún 2020.Ìpínlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kini ọdún 2020, àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn erankorona ni ó fa àrùn atégùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìlú Wuhan ní agbègbè Hube, orílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ fún àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019..
wikipedia
yo
ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 kéré púpọ̀ sí ìṣẹ̀lẹ̀ ti SARS tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2003, ṣùgbọ́n bí àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ṣe ń káká kiri pọ̀ púpọ̀ ní pàtàkì tí a bá wo iye àwọn tí wọ́n ti jẹ́ aláìsí.Àwọn àkókò tí àrùn yí ń ṣẹ́yọ àti ìgbésẹ̀ láti dẹ́kun rẹ̀.Oṣù kẹta ọdún 2020 ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ni wọ́n fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ múlẹ̀ tí wọ́n sì mú ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ kó àrùn yí lọ sí ibi ìyaraẹnisọ́tọ̀.Ìṣẹ̀lẹ̀ yí ṣẹlẹ̀ ní Mauritania, Olú-ìlú Noují sí ẹnìkan tí ó wá láti ìlú Okere tí wọ́n kò í ti dárúkọ orílẹ̀-èdè rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn tíìgbà abajade àwọn àyẹ̀wò dé pẹ̀lú ìdánilójú, wọ́n fagilé àwọn ọkọ̀ òfúrufú tí wọ́n ń lọ sí orílẹ̀-èdè Faranseni ojo kejidinlogun osu keta, Mínísítà fún ètò ìlera ti ìlú Mauritania kéde ṣíṣe àwárí ènìyàn kejì tí ó dájú wípé ó ní àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19..
wikipedia
yo
Ènìyàn yí jẹ́ arábìnrin àjèjì òṣìṣẹ́ kan tí ó ń ṣe iṣẹ́ ní ilé àwọn tọkọtaya kan tí wọ́n wá láti ìlú òkèèrè..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn ọjọ́ kẹwàá tí arábìnrin yí dé ni wọ́n ṣe àwárí ìṣẹ̀lẹ̀ yí lára rẹ..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkálẹ̀-àrùn erankokòró kẹta ni wọ́n kéde rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta pé ó ṣẹlẹ̀ sí bàbá Àgbàlagbà kan ẹni ọdún mẹ́rìnlénà tí ó jẹ́ ará ìlú Mauritania tí ó padà dé sí ìlú Mauritania ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta láti orílẹ̀-èdè Faranse pẹ̀lú ọkọ òfurufú ti ilẹ̀ Faranse.Orílẹ̀-èdè Mauritania ṣe Àkọsílẹ̀ ẹni àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ aláìsí ní ọgbọ̀n ọjọ́ kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
Ni ipari osu keta, isele mefa ni won fidi re mule nigba ti eniyan kan je alaisi, awon meji gba iwosan o wa seku eniyan meta ti won n se aisan lowolowo.osu kerin odun 2020 ni ojo kejidinlogun osu kerin, eniti o keyin lara awon ti o seku ti arun yi n baja lowolowo gba iwosan..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ ná a, wọ́n ti kọ́kọ́ fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ méje múlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Mauritania, èyí tí mẹ́fà nínú wọn ti gba ìwòsàn, tí ọ̀kan sì ti jẹ́ aláìsí..
wikipedia
yo
Eleyí i ló mú kí orílẹ̀-èdè Mauritania jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn orílẹ̀-èdè díẹ̀, tí wọ́n ń kojú àrùn yí ní àgbáyé, tí wọ́n gba òmìnira lọ́wọ́ àrùn COVID-19 fún ìgbà díẹ̀..
wikipedia
yo
Ni ojo kokandinlogbon osu kerin, omo orile-ede Sèga kan ni ayewo ti o daju fi han pe o ni ajakale-arun erankorona..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yí ni ti arábìnrin ọmọ ọdún mejidinlaadọrin kan tí ó ń gbé ní ìpínlẹ̀ Noufìlà..
wikipedia
yo
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun meji ni ó ṣẹlẹ̀ ní oṣù kẹrin, èyí tí ó mú kí iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ di mẹjọ..
wikipedia
yo
Laarin ojo kejidinlogun ati ojo kokandinlogbon osu kerin, ko si isele to n sele lowolowoo; arabinrin ti ayewo ti fi han pe o ni arun yi ni ojo kokandinlogbon osu kerin nikan ni arun yi n baja lowolowo ni ipari osu kerin.osu karun un odun 2020 ni ojo kefa osu karun un, pelu isele kan ti o n sele lowolowo, won mu ki ofin isemole rorun die..
wikipedia
yo
Nígbà tí Oṣù kàrún ún má a fi parí, àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ti gòkè lọ sí 480 tí àwọn tí ó ti jẹ́ aláìsí ti gòkè lọ sí mẹ́tàlélógún..
wikipedia
yo
Iye awon ti won fidi re mule pe won ni ajakale-arun yi ti lo soke si 530 ni osu karun un ti awon mẹtadinlọgbọn si ti gba iwosan.osu kefa odun 2020 awon isele tuntun 3,707 ni o waye ninu osu kefa ti o si mu ki iye awon ti won fidi re mule wipe won ni arun yi di 4,237..
wikipedia
yo
Ní ìparí Oṣù Kẹfà, àwọn ènìyàn 2612 ni wọ́n ń ṣe àìsàn lọ́wọ́lọ́wọ́.Ìtọ́kasí Mauritania..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ wípé ó ti tàn dé orílẹ̀-èdè dònà níníní ní oṣù kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àjọ Amnesty International jábọ̀ rẹ̀ wípé àwọn kan fòfin gbé àwọn oníròyìn tí wọ́n ń kọ nípa àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Niger, tí wọ́n sì ké sí ìjọba kí wọ́n dẹ́kun ìwà ìtẹ́ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn lójú mọ́lé.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kíní ọdún 2020, Àjọ Ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí Ìlera ní Àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní Kọfíd-19 ní orílẹ̀-m̀ Àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Iye ijamba ti arun korona ti fa lagbaye kere si iye ijamba ti aisan arun ọ̀fun SARS ti fa lati odun 2003, amo iye awon eniyan ti won to arun korona latari rírán ti o n ran kale ti.Po ju ti SARS lọ, bi o ti le je wipe itankale arun COVID-19 n gbópọn si lójojúmọ́ ti o si ti seku pa opolopo eniyan lagbaye.Bi o se n sele láwọn asiko kookanosu keta odun 2020-ede olominira Niger ni akosile akoko ni ojo kokandinlogun osu keta odun 2020, ni ilu *"Che..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó kó àrùn náà wọ orílẹ̀-èdè náà ní ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógójì..
wikipedia
yo
Wọ́n fidi rẹ̀ mule.wipe aláàárẹ̀ naa ti se irin-ajo lo si awon ilu bi Accra, Abidjan, Lomé ati Ouagadougou, saaju ki o to dari si orile-ede Niger.leyin ti iroyin arun yi kale ni orile-ede Niger, won ti awon pápákọ̀ ofurufu won pa lati tete dekun itankale arun naa.ẹnikẹta ti yoo ko arun yi wo orile-ede Niger ni obinrin omo orile-ede Brazil kan ti o wo orile-ede Niger ni 9jo kefa osu keta odun 2020.orile-ede Niger ti ni akosile ti o to meje lapapo nigba ti yoo fi di ojo karundinlogbon osu keta odun 2020, eni kan soso ni o papo da ni ojo kẹrinlelogun osu keta ni ilu opótiwa, ti alaisi naa si je omo odun mẹtalelọgọta ti o wa lati orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Àpapọ̀ iye àkọsílẹ̀ tí wọ́n padà rí ní orílẹ̀-èdè Niger ní inú oṣù kẹta jẹ́ mẹ́rìnlélọvon lápapọ̀, nígbà tí ènìyàn mẹ́ta papọ̀ dà nínú wọn..
wikipedia
yo