cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Èyí wá dín wọn kú sí mọ́kànlé.Oṣù Kẹrin ọdún 2020Wọ́n tún ní Àkọsílẹ̀ Iye ènìyàn tí ó tó forúkọsílẹ̀ tí wọ́n ní àrùn COVID-19, èyí sì mú kí Iye gbogbo àwọn aláìsàn korona ó di 719..
wikipedia
yo
Àwọn 452 rí ìwòsàn gbà nígbà tí àwọn 32 papọ̀ dá tí wọ́n gbòrun lọ..
wikipedia
yo
.Oṣù karùún ọdún 2020nínú oṣù yí, wọ́n tún ṣàwárí ọ̀tún nípa àwọn tí wọ́n ní kòkòrò àrùn COVID-9 tí wọ́n tò 239..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ggbogbo iye àwọn aláìsàn náà di 958 lápapọ̀, tí iye àwọn ti wọ di aláìsí di ìlọ́po méjì 64, tí àwọn 387 sì rí ìwòsàn gbà..
wikipedia
yo
Iye àwọn tó kù tí wọ́n kó kú tí wọn kò sì tíì gbádùn jẹ 55 ní ìparí oṣù karùún..
wikipedia
yo
.Oṣù kẹfà ọdún 2020nínú oṣù yí, wọ́n tún ṣàkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí ó tó ọgọ́rùún Knàà àti mẹ́tàdínlógún aláárẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí mú kí iye àwọn aláìsàn náà lápapọ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn náà ó gùnkè lọ sí tónítóníṣùgbọ́n..
wikipedia
yo
Iye awon ti ku je 67 nigba ti iye awon ti won ri iwosan gba je 943, ti iye awon to ku ti won ko ku ti won ko si tii gbadun je 65.Ẹ tun le wo COVID-19 tòótọ́ in Africa COVID-19 tòótọ́ by country and territoryawon itọkager..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 dé orílẹ̀-èdè Chad ní inú oṣù kẹta ọdún 2020.Bi ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kini ọdún 2020, àjọ ìtara tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní Tod-19 ní orílẹ̀-M Àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Amo iye awon eniyan ti won to arun korona latari rírán ti o n ran kale ti.Po ju ti SARS lo, bi o ti le je wipe itankale arun COVID-19 n gbópọn si lójojúmọ́ ti o si ti seku pa opolopo eniyan lagbaye.Bi o se n sele law9n asiko kookanosu keta odun 2020ni ojo kokandinlogun osu keta, ijoba orile-ede Chad fidi isele arun korona akoko mule, ti eni akoko naa si je ero 9ko Morocco ti o sa kuro ni ilu Douala.Ni ojo kerindinlogbon osu keta, won ti fidi isele arun korona ti o to meta mule ni orile-ede Chad..
wikipedia
yo
Ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn aláìsàn náà jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Chad ti ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju mejidinlaadọta lọ..
wikipedia
yo
Ẹnìkejì ní ọmọ orílẹ̀-èdè Cameroon ti ọjọ́ ori rè ko ju ọdún márunlé lo ti ó jẹ́ èrò ọkọ̀ òfúrufú Ethiopia tí ó ń darí bọ̀ láti ìlú àṣàgbá, Brussels àti Addis Ababa.Ní Ọgbọ̀njọ́ Oṣù mẹ́ta, wọ́n tún fìdí àwọn ènìyàn tí ó ti kó àrùn korona méjì míràn múlẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹni akọkọ ni ọmọ.orilẹ-ede Chad ri de lati ilu Douala , ri ẹnikeji si jẹ ọmọ oriṣi Switzerland ti o n bọ lati ilu Brussels.Àkọsílẹ̀ meje péré ni wọn ri ni inu oṣu kẹta, nigba ti wọn ko pàdánù ẹnikọ̀kan, bẹ́ẹ̀, ko si ẹnikẹni ti ara rẹ̀ ya ti o si pada silẹ rẹ.Oṣù kẹrin ọdun 2020 ni ọjọ keji osu kerin, wọn tun ni akosile kan ti o je ọmọ orilẹ-ede Chad ti n bo lati ilu Dubai sugbon ti o gba ilu Abuja ni orile-ede Naijiria koja.Ni ojo keta osu keta, ẹlomiran naa tun ko arun yi wọ orile-ede Chad ẹni ti o jẹ ọmọ orile-ede Faranse ti o n bo lati ilu Brussels, amo ti o gba ilu Paris koja-ede Chad tun ni akosile tuntun ti o je ti abele..
wikipedia
yo
Ọmọ.Orílẹ̀-èdè Chad kan ti o jẹ ẹni odun mọkanlelọgbọn ti o ti ni ìfara-rà pẹlu ọmọ.Orílẹ̀-èdè.Chad. miran.ti oun ti ni kòkòrò àrùn korona tẹ́lẹ̀.Ni Ojw Kẹ́sà osu keta yi kan naa, awon osise ilera fi enikan ti o je omo orile-ede Chad ti o n bo lati orile-ede Pakistan, ti o gba orile-ede Cameroon koja ki o to de ilu kan ti won n pe ni n’jamena..
wikipedia
yo
Ilu Aitache ni won ti rọ́wọ́ to nigba ti won ṣayẹwo ẹjẹ re ni ojo kerin osu keta ti esi ayewo re si fidi re mule wipe o ti ni kokoro arun korona leyin ojo kerin ti won ti fi si iyara adá.during April there were 66 New cases, bringing the total number of confirmed cases to 73..
wikipedia
yo
Two deaths were reported on 28 April and three more on 30 April, bringing the total death toll to five..
wikipedia
yo
33 Patipòọ Recoks, Leaving 35 active Ced at the End of the Month.Oṣù Kárùún ọdún 2020Iye àwọn ènìyàn tí ó kó àrùn yí ní inú oṣù yí jẹ́ àjọọdún lápapọ̀, tí iye ènìyàn ti gbémìmi jẹ́ 65, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n ìmúláradá jẹ́ “Oṣù.Oṣù kẹfà ọdún 2020Wọ́n ṣàwárí iye ènìyàn tí ó tó méjì dín lógoan tí wọ́n ní àrùn korona nínú oṣù yí tí ó sì mú kí iye àwọn tí wọ́n ní àìsàn yí.Láti ìbẹ̀rẹ̀ oṣù kẹta ó jẹ́ 866, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n jẹ́ aláìsí lápapọ̀ jẹ́ 74, tí àwọn 781 sì gba ìwòsàn padà sí ilé wọn láyọ̀ àti àlàáfíà..
wikipedia
yo
Iye awon ti won ko tii ri iwosan gba ti won ko si ku je mokanla pere ni ipari osu kefa odun 2020.Awon igbese ti ijoba ile Chad gbe lati dekun itankale arun yi siwaju si, won fagile gbogbo ìgbòkègbodò irina oko ofurufu pata, yato si eyi ti o ba ko eru nikan.Ẹ tun le wo COVID-19 47 tòótọ́ in Africa COVID-19 tòótọ́ by Country and territoryawon itọkasiawon Ìtàkùn ìṣẹ́gun Chad..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-9 de orílẹ̀-èdè Kamẹrúùnù ní inú oṣù kẹta ọdún 2020.Bi ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kini ọdún 2020, àjọ ìtara tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní Bori-19 ní orílẹ̀-M àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó ń ran kalẹ̀ tí.pọ̀ jù ti SARS lọ, bí ó ti lé jẹ́ wípé itankale àrùn COVID-19 ń gbópọn sí lójojúmọ́ tí ó sì ti seku pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lagbaye,àwọn àsìkò kọ̀kan tí ó ṣẹlẹ̀ kẹta ọdún 2020 (ajakalè COVID-9 wọ orílẹ̀-èdè Cameroon ní ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹta ọdún 2020 nígbà tí wọ́n ní akosile àkọ́kọ́ lati ara ẹnìkan tí ó ti ní àrùn yí tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Faransé tí ó wọ́ ìlú Yaoundé ní orílẹ̀-èdè Cameroon ní ojo kẹrinleloguńnlélógún Oṣù kejì..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ Kejì ni wọ́n kéde rẹ̀ ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta lára ẹnìkan tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Cameroon tí ó ti ní ìfara-rà pẹ̀lú ẹni àkọ́kọ́ tí kọ́kọ́ kó àrùn náà wọ Cameroon tẹ́lẹ̀.Wọ́n tún ní àkọsílẹ̀ márùún míràn ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wón kò fi ìtọ́ka kankan lédè nípa àwọn ènìyàn náà.Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀-èdè Cameroon ìyẹn Dókítà Malachie manaouda, sọ wípé àrùn náà ń gbilẹ̀ sí lójoojúmọ́ ni pẹ̀lú bí wón tún ṣe rí àkọsílẹ̀ Mélé Akẹtàdínlógún mìíràn ti mẹ́fà wà.Láti Yaoundé, mẹ́sàán láti ìlú Douala, tí ẹyọ̀kan sì wà láti Bafoussam.Ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, wọ́n ti ní àkọsílẹ̀ tí ó tó mọ́kànlo-ipo..
wikipedia
yo
mẹ́talélọ́gọ́ta lati Yaoundé, márùndínlọ́gbọ̀n ní Douala, ti mẹ́ta sì wà láti baafoussam.Gbogbo iye àwọn aláìsàn COVID-9 lápapọ̀ nínú oṣù kẹta jẹ́ ọgọ́rùún kan ó lé méjìlélógójì ní ìparí oṣù kẹta, nígbà tí iye àwọn ènìyàn mẹ́fà papò dà.Oṣù kẹrin ọdún 2020nígbà tí yóò fi di ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin, iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti kó àrùn COVID-9 jẹ́ ọgọ́rùún méjì àti mẹ́fàlọgọjọ.Àrùn náà sì tún mú iye ènìyàn tí ó ọgọ́rùún mẹ́fà àti méjìdínlọ́gọ́ta ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin.Ó tún gòkè sí ní ọjọ́ keje oṣù yí kan náà ólú iye tí ó tó ọgọ́rùún mẹ́fà àti márùndínloan.Ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹrin, ó tún gòkè sí pẹ̀lú iye tí ó tó ọgọ́rùún méje àti ọgbọ́n.Ní ọjọ́ ikalélógúnlélógún oṣù kẹrin, wọ́n ti ní àkọsílẹ̀ tí ti tó ẹgbẹ̀rún kan olè ọgọ́rùún àti mẹ́tàlá àti mẹ́tàlá tí wọ́n ti lu gùdẹ̀ àrùn náà ní orílẹ̀-èdè Cameroon..
wikipedia
yo
Iye àwọn tí wọ́n kó àrùn náà ni u oṣù kẹrin lápapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́jọ àti méjìlélọ́gbọ̀n..
wikipedia
yo
Iye àwọn ènìyàn tí wọ́n gba ìwòsàn lápapọ̀ jẹ́ ọgọ́rùún mẹ́sàán ó lé mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n, nígbà tí Iye ènìyàn tó kú tí kò ti rí ìwòsàn gbà tí wọ́n kó sí papọ̀ dá jẹ́ ọgọ́rùún mẹ́jọ ó lé mẹtadinlogoji.Oṣù Karùún ọdún 2020Wọ́n ní àkọsílẹ̀ ti tó ẹgbẹ̀rún méjì àti mẹ́rìnbáàrùún, tí ènìyàn mẹ́rìnlélọ́gọ́ta sí ìgbe mi..
wikipedia
yo
Iye àkọsílẹ̀ tí wọ́n ní nínú oṣù kẹrin jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin méjìlélọ́gọ́rin tí ó sì mú kí àkọsílẹ̀ náà tó ẹgbẹ̀rún márùún àti mẹ́rìnhelikaian..
wikipedia
yo
Iye àwọn ènìyàn tí wọ́n gba ìmúlára dá lápapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti ọgọ́rùn márùún ó lé méjìdínlógóje.Oṣù karùún ọdún 2020Wọ́n rí àkọsílẹ̀ tí ó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ó lé méjìdínlógóje, nígbà tí iye àwọn ènìyàn ti rí ìwòsàn gbà jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lápapọ̀..
wikipedia
yo
Iye awon eniyan ti ko ku ti ko si gbadun je egberun meji ati ọgọ́rùún kan o le mọ́kàndínlọ́gọ́jọ.Àkọsílẹ̀ iye eniyan to ti papo daosu keta odun 2020eni akoko ti koko gbẹ́mìí mì ku ni ojo kẹrinlelogun osu keta..
wikipedia
yo
The deceased was the famous Saxophonist Manu dibango..
wikipedia
yo
By the end of March six persons had died from COVID-19.Oṣù kẹrin ọdún 2020eniyan mẹrindinlaadọrin ni ó papò da ninu osu kerin.tí ó sì jé kí gbogbo rẹ̀ ó bọ́ sí mọkanlelọgọta.Oṣù Karùún ọdún 2020iye ènìyàn tí ó kú nínú oṣù Karùún jẹ́ ọgọ́rùún kan àti ọgbọ́n tí ó mú kí gbogbo iye ènìyàn ti papò dà ó jẹ́ 191.Oṣù kẹfà ọdún 2020àwọn ọgọ́rùún kan olè méjìlélógún ènìyàn ló kù tí ó mú kí gbogbo iye ènìyàn ti papò dà ó jẹ́ ọgọ́rùún kan ó lé mẹ́tàlélọ́gọ́ta lápapọ̀.Ìrànwọ́ òògùn àti irinṣẹ́ ÌleraỌ̀gbẹ́ni Jack ma ṣe ìrànwọ́ nípa fífi àwọn nkan irinjù ìlera ìgbàlódé bí irinṣẹ́ tí ó tó 9 lọ́nà lọ́nà ogun, ìbojú tí ó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùún àti àwọn irinṣẹ́ bo àwọn òṣìṣẹ́ ìlera míràn tí ó tó ẹgbẹ̀rún kan láti gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn korona ní ilẹ̀ Áfíríkà the olùdaríplies to Cameroon's to Cameroon's Airport on 27. –gbaju àgbà ( Àgbà bọ́ọ̀lù gba ìyẹn Samuel to'ó ṣe ìrànwọ́'ó ṣe ìrànwọ́ tí ó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta fún àwọn ọlọ́kọ̀ ní ìlú rẹ̀.Ìgbésẹ̀ àwọn ìjọba ní ọjọ́ kejì Oṣù kẹta oṣù kẹ́ta lóríṣìíríṣìí ti ó jẹ́ tí ó jẹ́ olórí fún orílẹ̀-èdè tálákà pàṣẹ pé kí wọ́n tí gbogbo ibodè tí ó wọ ìlú wọn fún ìlú wọn fún ètò ìléra rẹ̀ ní ó ní O jọ Oṣù kẹrin yóò òṣìṣẹ́ yóò lọ láti di láti ojúlé sí ojúlé láti ṣàyẹ̀wò àrùn-9 fún àwọn ènìyàn ní láti tètè ní
wikipedia
yo
Ni ojo keje osu kerin, ijoba orile-ede Cameroon Kora-ro lori Ìtọrọ ìrànwọ́ lọ́wọ́ awon laami-laaka lágbàáyé ati awon ọ̀tọ̀kùlú-ìlú lati gbógun ti ajakale arun COVID-9..
wikipedia
yo
Ìgbésẹ̀ yi mu ìkùnsínú wá láti ọ̀dọ̀ àwọn ará ìlú lọpọlọpọ ọ̀nà, tí wọ́n sì li ìgbésẹ̀ náà mọ́ ẹbọ òṣèlú.Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹrin yí kan náà ni ìjọba orílẹ̀-èdè Cameroon gbé ìgbésẹ̀ onípele méje kan láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn korona ní orílẹ̀-èdè wọn..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ni Djibouti wa ní ara àjàkálẹ̀-àrùn erankorona 2019 (COVID-19) tí ó ń ja káàkiri èyí tí àrùn atégùn erankorona 2 (SARS-CoV-2) ń fa..
wikipedia
yo
Kòkòrò àrùn fáírọ́ọ̀sì yí tànkálẹ̀ dé orílẹ̀-èdè Djibouti ní oṣù kẹta ọdún 2020ìpínlẹ̀ oríṣiríṣi àwọn orílẹ̀-èdè tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí i alágbára ní àgbáyé ni àwọn ológun wọn ní ibùjókòó ti ológun sí orílẹ̀-èdè Djibouti, lára wọn ní orílẹ̀-èdè China, Faransé, Italy Japan àti United States of America..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ tí wọ́n fi múlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Djibouti ní ti ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ológun ti orílẹ̀-èdè Spanish èyí tí ó mú kí wọ́n kó gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ológun ló sì ìfipamọ́ ní ilé-ogun tí àwọn ológun Faranse tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Djibouti.Àwọn àkọ́kọ́ tí àrùn yí ń ṣẹ́yọ.Oṣù Kẹta ọdún 2020 ní ọjọ́ keke Oṣù Kẹta, ní ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ tí COVID-19 wáyé ní orílẹ̀-èdè Djibouti latipase ọkàn ninu awon omo egbe ológun ti ìlú Spanish eni tí ó bawon de fún ise Atalanta ní ojo kerinla osu keta tí àyẹ̀wò tí wọ́n se fun un ni ojo ketadinlogun osu keta fihan pé ó ní àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19..
wikipedia
yo
Ọmọ ogun tti ó ní ìkọlù àrùn yí kò ì tì ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn olùgbé ní agbèègbè..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Spain kede wípé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ọmọ ogun yí i ni wọn yí ọ fipágbé padà sí ìlú wọn..
wikipedia
yo
Alágbàṣe kan ti o n sise fun eeka ti o n ri si aabo ti ile-ise ologun ti ile Amerika eyi ti o wa ni ago Lemonnier, ti i se ìpàgọ́ ologun ile Amerika kan soso ti o tobi julo ni orile-ede Djibouti, ni ayewo fidi re mule pe o ni ajakale-arun COVID-19 ni osu kanna..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ ọgbọ̀n ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ ní òpin Oṣù Kẹta.Oṣù Kẹrin ọdún 2020 ní ọjọ́ kejì Oṣù Kẹrin, Báńkì Àgbáyé (World Bank) fi ọwọ́ sí miliọnu marun un dọ́là owó ilẹ̀ Amẹ́ríkà, láti inú ìmọ́ ọwọ́ pàjáwìrì, fún orílẹ̀-èdè Djibouti gẹ́gẹ́ bi Arapa Iṣẹ́ àkànṣe fún àmójútó àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Djibouti..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ karùn ún oṣù kẹrin, àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti ṣẹ́yọ ti gòkè lọ sí mọ́kàndínlọ́gọ́ta..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹ̀sán án Oṣù Kẹrin, orílẹ̀-èdè Djibouti ṣe Àkọsílẹ̀ ẹni àkọ́kọ́ tí àjàkálẹ̀-àrùn erankokòró pa..
wikipedia
yo
Awon eniyan ogoje (140) ni won ti ko arun COVID-19, nigba ti awon mejidinlogbon ti gba iwosan..
wikipedia
yo
Ni ojo ketalelogun osu kerin, iko omo ogun Amerika ti won wa ni Djibouti kede ilera pajawiri fun gbogbo eniyan..
wikipedia
yo
Ni ojo kẹrinlelogun osu kerin, orile-ede Djibouti ni o ni itankale ti o po julo ni ile Afirika..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ kejì tí ó ṣẹlẹ̀ ní Àgọ́ Lemonnier ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní òpin Oṣù Kẹrin, èyí tí ó fa ìdédé ìdédé.àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tuntun 1059 ni ó ṣẹlẹ̀ ní Oṣù kẹrin, èyí tí ó mú kí ní Iye àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ yí lọ sí 1089..
wikipedia
yo
Awon eniyan meji lo ti je alaisi latipase COVID-19, nigba ti awon eniyan 642 ti gba iwosan ti awon eniyan 445 si n gba itoju lowolowo ni opin osu kerin.osu karun un odun 2020 ni osu karun un, isele tuntun 2265 ni o sele eyi ti o mu ki iye awon isele ti won fidi re mule goke lo si 3354..
wikipedia
yo
Iye awon ti o ti je alaisi lo soke si merinlelogun..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan goke lati 862 lo si 1504 ti o si wa seku awon eniyan 1826 ti won n gba itoju lowolowo ni opin osu karun un.osu kefa odun 2020 awon isele tuntun 13 ni o sele ninu osu kefa, eyi ti o mu ki apapo iye awon isele ti won ti fidi won mule di 4682..
wikipedia
yo
Iye àwọn tí ó ti jẹ́ aláìsí ti di mẹrinlelaadọta (54)..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan goke lati 3020 lo si 4524 ti o si wa seku awon eniyan 104 ti won n gba itoju lowolowo.osu keje odun 2020igbese ijoba lati dawo isele COVID-19 duro ni ojo karundinlogbon osu keta, orile-ede Djibouti ti kede pe gbogbo awon oko ofurufu ti won n rin irin-ajo ni won ma a daduro bere lati ojo kejidinlogun osu keta..
wikipedia
yo
Wọ́n tún dá àwọn ọkọ̀ ojú-irin dúró ní ogúnjọ́ oṣù kẹta..
wikipedia
yo
Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) ti pèsè ohun èlò ààbò ti ara ẹni fun àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Djibouti..
wikipedia
yo
Ijoba ti kede titipa awon ile-eko ati awon ibi ijosin ni ojo kokandinlogun ati ojo kejilelogun osu keta ni atele..
wikipedia
yo
Wọ́n ti kọ́kọ́ kéde isemole fun gbogbo awon omo orile-ede Djibouti ni ojo ketalelogun osu keta ki o to di wipe won sun un siwaju di ojo kejo osu karun un.Ìtọ́kasí Djibouti..
wikipedia
yo
Arun COVID-19 de si orile-ede Togo ni osu keta odun 2020.Bi o se bere ni ojo kejila osu kini odun 2020, ajo isokan ti o n ri si ilera ni agbaye fidi arun korona ti a tun n pe ni Kofid-19 ni orile-m agbaye ni ojo kejila osu kinni ni odun 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tó ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé létí..
wikipedia
yo
Iye ìjàmbá tí àrùn korona ti fa lagbaye kéré si iye ìjàmbá ti àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fa lati ọdún 2003, àmọ́ iye àwọn ènìyàn ti wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó n ran kalẹ̀ ti.Pọ̀ ju ti SARS lọ, bi ó ti lè jẹ́ wípé ìtànkálẹ̀ àrùn COVID-19 n gbópọn si lójojúmọ́ tí ó sì ti ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lágbà.Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ láwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta, orílẹ̀-èdè Togo ni àkọsílẹ̀ àkọ́kọ́ àrùn COVID-19..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó kó àrùn náà wọ orílẹ̀-èdè náà jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Togotí ó jẹ́ ọmọ ọdún méjì lélógójì..
wikipedia
yo
Wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé aláàárẹ̀ náà ti ṣe ìrìn-àjò lọ sí àwọn ìlú bí Germany, France, Turkey àti Benin, ṣáájú kí ó tó darí padà sí orílẹ̀-èdè Togo..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Togo ti ni àkọsílẹ̀ mẹjọ lapapọ awọn ti o ni arun naa nigba ti yoo fi di ọjọ ogun Oṣu Kẹta ọdun 2020..
wikipedia
yo
Arabinrin ti o kọkọ ko arun naa si ti ri iwosan gba..
wikipedia
yo
Ni ojo kokanlelogun osu keta, won ti awon pápákọ̀ ofurufu won pa lati tete dekun itankale arun naa leyin ti won rii awon eyan meje ti o tun ko arun naa..
wikipedia
yo
Awon ara ilu Lomé, Tsevie, Kpálì ati Sokode wa ni igbele fun ose meji lati ojo ogun osu keta..
wikipedia
yo
Ni ojo ketadinlogbon osu keta, eyan kan papo da lati ara arun naa..
wikipedia
yo
Ní ìparí oṣù kẹta, wọ́n ti ríi àwọn èèyàn mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tí ó kó àrùn náà, tí èèyàn kan ṣoṣo sì papò dà, àwọn mẹ́wàá sì rí ìwòsàn gbà..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹrin, wọ́n ríi àwọn èyàn méjìlélọ́gọ́rin tí ó tún kó àrùn náà, èyí sì jẹ́ kí gbogbo àwọn tó ti kó àrùn náà jẹ́ 116..
wikipedia
yo
Awon eyan mesan si papo da, awon eyan 65 si ri iwosan gba.Ni osu karun-un, awon eeyan 326 tun ko arun naa, eyi si je ki gbogbo awon to ti ko arun naa je 442..
wikipedia
yo
Àwọn èèyàn mẹ́rin kú ní Oṣù náà, èyí sì jẹ́ kí gbogbo àwọn ti papọ̀ dá jẹ́ mẹ́tàlá, àwọn èyàn 211 sì rí ìwòsàn gbà..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹfà, wọ́n ríi àwọn èyàn 208 tí ó tún kó àrùn náà, èyí sì jẹ́ kí gbogbo àwọn tó ti kó àrùn náà jẹ 643..
wikipedia
yo
Èèyàn kan kú ní oṣù náà, èyí sì jẹ́ kí gbogbo àwọn ti papò dà jẹ́ mẹ́rìnlá, àwọn èyàn gbogbowọ́n sì rí ìwòsàn gbà..
wikipedia
yo
Àwọn èèyàn 234 síi ní àrùn náà ní ìparí oṣù náà.Ní oṣù kẹsàn ọdún 2021, Togo n gbòòrò sí ipò pàjáwìrì ìlera títí di oṣù kẹsàn 2022 ní àtẹ̀lé ìgbésókè ni àwọn ọ̀ràn tuntun ti coronavirus ní àwọn ọ̀sẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀..
wikipedia
yo
wiwọle si awọn ile iṣakoso jẹ kókó ọrọ si igbejade ti ìkọjá àjẹsára COVID-19 kan.Awon itọkasitògotògo..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-9 de orílẹ̀-èdè Cape Verde ní Oṣù Kẹta ọdún 2020.Bi ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kini ọdún 2020, àjọ ìtara tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní Baga-19 ní orílẹ̀-M àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó ń ran kalẹ̀ tí.pọ̀ jù ti SARS lọ, bí ó ti lé jẹ́ wípé itankale àrùn COVID-19 ń gbópọn sí lójojúmọ́ tí ó sì ti seku pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lagbaye, Model-based Síroko, for Cape Verde suggest that the 95% confidence interval for the time-var re number on t has been flukánkánating around around.2 Since since April 2020.Àwọn àsìkò kọ̀kan tí ó ṣẹlẹ̀ kẹta ọdún 2020 ní ogunjo Oṣù kẹta, orílẹ̀-èdè cape ni akosile COVID-9 àkọ́kọ́, tí ẹni tí ẹni tí ó kó naa je eni mejidinlogota tí ó sì tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ọmọ-ede United Kingdom.Ni ojo keji, wọ́n tún ní akosile meji miran, tí àwọn àrùn naa mu je arin-ajo afẹ̀kan lati United Kingdom ti ojo ori orí kini jẹ́ ọdún méjìdínlọ́gọ́ta tí ẹnìkejì sì jẹ́ ọmọ ọgọta ọdún..
wikipedia
yo
Awon mejeji yi ati eni akoko ni won jo wa ni Bomber vista the first death was announcedni ojo karùnlog on osu keta, won tun ni akosile elemerin ti alaisan naa je eni odun mẹtalelogoji, ti o si je omo.Orílẹ̀-èdè cape Verde ti o dari Wale lati Europe, ti won si ṣayẹwo fun ni olu-ilu Praia, ni Erekusu Santiago.Ni ojo keji,Minisita fun eto ilera ni orile-ede cape Verde kede re wipe iyawo eni akoko ti o ni arun korona naa ti fara kàṣà aisan naa pelu..
wikipedia
yo
tí obinrin náà sì jẹ́ ẹnikẹ́ni àkọ́kọ́ tí yóo ní àrùn náà láì rin ìrìn-àjò kan kan..
wikipedia
yo
Wọ́n ní akosile karùún ní ìpari oṣù karùún ọdún, 2020, nígbà tí ènìyàn kan ṣoṣo ti papo dá tí ó sì ṣe kù àwọn mẹ́rin Dondo.Oṣù kẹrin ọdún 2020 nínú Oṣù kérin, wọ́n ti ní akosile ọgọ́rún kan ó lé mẹ́rìndínlógún mìíràn, ti apapo iye ògbẹta tí ó ti ní àrùn yí tí Kétò sí ìránwèwè kan o lé máka mọ́kàndínlógún..
wikipedia
yo
Kò sí ẹlòmíràn tó kú mọ́ yàtọ̀ sí ẹni àkọ́kọ́ tó kú ,nígbà tí àwọn mẹrin rí ìwòsàn gbà tí wọ́n sì pada sílé wọn..
wikipedia
yo
Ó wá ku àwọn ènìyàn ọgọ́rùún kan àti mẹ́rìndínlógún tí àrùn náà sì wà lára wò níparí oṣù kẹrin.Oṣù karùún ọdún 2020 nínú oṣù karùún, orílẹ̀-èdè Cape Verde tún ní àkọsílẹ̀ ènìyàn tí iye wọn ti ọgọ́rùún mẹ́ta àti mẹ́rìnlélógún tí wọ́n tún fara kó àrùn náà..
wikipedia
yo
Àwọn mẹrin ló ṣaláìsí, nígbà tí àwọn eniyan ọgọ́rùún kan ati mọkandíndinan gba ìwòsàn ti wó sí lọ sí ilé wọn láyọ̀..
wikipedia
yo
Iye awon to ku ti won ko ti gbadun je igba o din meje eniyan.osu kefa odun 2020 Cape Verde ni akosile eniyan ti o to ọgọ́rùún mejo o din mejo ti won ti ni arun COVID-9, ti o mu ki iye awon alaisan naa lapapo o je egberun kan ati ọgọ́rùún meji o le mejilelogun..
wikipedia
yo
Iye àwọn tí ó kú láti ìbẹ̀rẹ̀ jẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún, nígbà tí yẹ àwọn ènìyàn tó rí ìwòsàn gbà jẹ́ ọgọ́rùún mẹ́fà àti mọkandinlọgbọn..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọn kò tíì gbádùn tí wọn kò sì kú jẹ́ ọgọ́rùún maruun ati ògoṣáan ó dín mẹjọ..
wikipedia
yo
Ní ìparí osù kẹfà.Àwọn ìgbésẹ̀ ìdènà àjàkálẹ̀ àrùn náàLáti inú oṣù kẹta, gbogbo àyẹ̀wò àrùn tí.Wọ́n ti ṣe fún àwọn ènìyàn ni ó jẹ́ wípé wọ́n kò pé ìjọba ilẹ̀ òkèrè dá sí rárá..
wikipedia
yo
Àmọ́ ṣá, wọ́n fàyè gba ọkọ̀ òfúrufú tí ó bá kó ẹrù nìkan kí ó palẹ̀ sí pápákọ̀ òfúrufú wọn..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wo tún fàyè gba àwọn ọmọ.Orílẹ̀-èdè mìíràn tí wọ́n bá nífẹ láti padà sí orílẹ̀-èdè wọn..
wikipedia
yo
Ìjọba orílẹ̀-èdè Cape Verde fún ìgbà àkọ́kọ́ kéde kónílé-o-gbélé tí ó jẹ́ ti pàjáwìrì ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 2020, léte àti mú àdínkù bá ìfara-ràra àwọn ènìyàn tí on mú àrùn náà pọ̀ sí..
wikipedia
yo
Ìgbésẹ̀ yí ṣe àkóra lọ́pọ̀lọpọ̀ fún okòwò àwọn ènìyàn àti ti ìjọba fúnra rẹ̀.Ẹ tún le wo COVID-19 Siria in Africa COVID-19 tòótọ́ by Country and territoryàwọn ìtọ́kasí àjàke àrùn COVID-9àwọn ìtàkùn ìjásóde Instituto Nacional de sáùde Publica – Cape Verde's Public Health National InstituteCOVID 19 — Corona virus - Official site about COVID-19 in Cape Vermúniwọlévirus tòótọ́cape Verilape Verdedisease outbreaks in Cape Verde..
wikipedia
yo
Awon ara Georgia (K`artvàáké) — eya eniyan ati orile-ede eniyan ni Georgia.itọkasi.Eastmond, Anthony (2010), Royal Imagery in medieval Georgia, Penn State Presssun, R..
wikipedia
yo
(1994), The making of the Georgian Nation, Indiana University PressLang, D..
wikipedia
yo
(2016) The Sasa© World through Georgian Eyes, CaucAsia and the iraSarahẹ́múlà Commonwealth in late Antique Georgian Literature, Sam Houston State University, USA, Routledgetoumanoff, C..
wikipedia
yo
(1963) Studies in Christian Caucasian History, Georgetown University PressGeorgia àwọn ará Europeàwọn ará Asia..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-9 wọ orílẹ̀-èdè Gàbọ̀n ní inú oṣù kẹta ọdún 2020.Bi o ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kíní Ọdún 2020, Àjọ Ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún n pe ní Baga-19 ní orílẹ̀-M Àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tó ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé létí wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ síwájú sí wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, òun ni ó ń fa ìfunpínpín ní ní inú káà ọ̀fun àti àyà, tí ó sì ma ń fa kátà tàbí kí ènìyàn ó má wú ikọ̀ tàbí sìn léra léra..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó ń ran kalẹ̀ tí.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lé jẹ́ wípé itankale àrùn COVID-19 ń gbópọn sí lójojúmọ́ tí ó sì ti seku pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lagbaye,àwọn àsìkò kọ̀kan tí ó ṣẹlẹ̀ kẹta ọdún 2020won kede akosile ajakale àrùn korona tí a tún mọ̀ sí COVID-9 ní orílẹ̀-èdè Gabon ní ojo kejìlá Oṣù kẹta ọdún 2020, lára ìkan nínú ọmọ orílẹ̀-èdè wọn ti ojo ori rẹ̀ kò ju mẹtadinlọgbọn lo ti o sese de lati orile-ede Faransé..
wikipedia
yo
Leyin ojo me ona ti o de ni won to fidi arun naa mule lara re.Ni ojo ketalelogun osu keta, won tun ṣàwárí awon meji miran ti won ti ni arun yi, ti o fi mo obinrin kan ti o n sise ni ile-ise ijoba ti o n ri si ìbáṣepọ̀ orile-ede Gabon ni ile okere..
wikipedia
yo
Ẹnìkẹta jẹ́ Ọlọpa ti ọjọ́ oti rẹ̀ kò ju ọdún mọkandinlọgbọn tí ó ń ṣiṣẹ́ ní pápákọ̀ òfúrufú Leon-mbá International Airport..
wikipedia
yo
Oun lo ye iwe-ìrìnà eni akọkọ ti ko arun naa wọ orilẹ-ede Gabon nigba ti o n bo lati orile-ede Faranse ni ojo kejo osu keta odun 2010.Ni ogunjo osu keta, orile-ede Gabon ni akosile eni akoko ti o papo da.Ni ojo kẹrinlelogun, osu keta, ile-ise ijoba ti o n ri eto ilera tete mo ìṣàyẹ̀wò arun COVID-9 pelu bi arun naa se n gbilẹ si ni orile-ede Gabon..
wikipedia
yo
Lára rẹ̀ ni ẹni ọdún marundinlaadọta tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Togo, àmọ́ tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Gabon tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ darí dé láti orílẹ̀-èdè Senegal ni ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹta..
wikipedia
yo
Ẹlòmíràn naa tun ni eni ti o je omo orile-ede Gabon, amo ti o sese de lati orile-ede Faranse ni ojo kokandinlogun osu keta.laarin osu yi, won ti ni akosile meje miiran, enikan papo da, bee ni o ku awon mefa ti won ku.osu kerin odun 2020ninu osu kerin, iye awon eniyan ti o to egberun meji ati ọgọ́rùún mefa o le mẹ́sàán..
wikipedia
yo
Tí ó sì ku àwọn ọgọ́rún méjì ó lé mẹ́fà ní ìpari Oṣù kérin.Oṣù karùún ọdún 2020nínú oṣù Karùún, wọ́n tún ní akosile ẹgbẹ̀rún meji àti ọgọ́rùún mẹ́ta ó lè mọkandilọ́gọ́jọ, tí ó mú iye àwọn tí ó ti kó àrùn korona l9 sí ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùúnpọ̀ mẹ́fà ó lé márùndínlọ́gọ́ta..
wikipedia
yo