cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Iye àwọn tí wọ́n rí ìwòsàn gbà jẹ́ ọgọ́rùún méje ó lé mejilelogun.Oṣù Kẹfà Ọdún 2020ninu Oṣù Kẹfà, wọ́n tún ní Àkọsílẹ̀ tí ó tó ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùún méje ó lé ìtẹ́wọ́gbà..
wikipedia
yo
Iye awon ti won ri iwosan gba je egberun meji ati ọgọ́rùún merin o le ogun.Oṣù keje odun 2020ninu osu keje, orile-ede Gabon fopin si fiFonte lu iwe ìrìnà awon eniyan ti won fe lati wa si Gabon lati awon orile-ede Europe ati awon orile-ede miran ti arun naa ti gbilẹ julo.Ẹ tun le wo COVID-19 tòótọ́ in Africa COVID-19 0 by country and territoryawọn itọsìgáese'
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta.Ìpínlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kini ọdún 2020, àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn erankorona ni ó ń fa àrùn atégùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìlú Wuhan ní agbègbè Hube, orílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ fún àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 2019.Ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 kéré púpọ̀ sí ti àrù́n SARS tí ó ṣẹ́yọ ní ọdún 2003 ṣùgbọ́n bí àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ṣe ń tàn káríayé pọ̀ púpọ̀ ní pàtàkì tí a bá wo iye àwọn tí ó ti jẹ́ aláìsí.àwọn àkókò tí àrùn yí n ṣe kẹta ọdún 2020 ní ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù Kẹta, ìsẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à ní wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní Asmara, ẹni tí ìsẹ̀lẹ̀ yí ṣẹlẹ̀ sí ní ọmọ orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à tí ó sẹ̀sẹ̀ dé láti orílẹ̀-èdè NORWAY.Ìṣẹ̀lẹ̀ márùndínlógún ní wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní Oṣù Kẹta tí gbogbo wọn sí ń gba ìtọ́jú títí di òpin Oṣù Kẹta yí.Oṣù Kẹrin ọdún 2020 orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à kéde isemole ọlọ́jọ́ mọ́kànròyìn bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejì oṣù kẹrin..
wikipedia
yo
Iselowo yi ni won tun se afikun re siwaju si.Ni ojo kesan an osu kerin, orile-ede Eritrea se akosile isele arun COVID-19 tuntun meji ti o sele si awon omo orile-ede won an meji ti won ti pada si orile-ede Eritrea ki o to di wipe won fi ofin de lilo ati bíbo oko ofurufu..
wikipedia
yo
Ọ̀kan jẹ́ ọmọ ọgbọ̀n ọdún nígbà tí èkejì sì jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélọ́gọ́ta..
wikipedia
yo
Apapo iye awon ti won ti wa ko arun COVID-19 ni orile-ede Eritrea di mẹtalelọgbọn..
wikipedia
yo
Apapo iye awon isele ti won fidi re mule di mokandinlogoji ni osu kerin, eyi ti o fi merinlelogun ju isele ti osu keta lo..
wikipedia
yo
Mẹ́wó ninu àwọn aláìsàn mọkandinlogoji gba iwosan ní oṣù kerin, ó wá ṣekú àwọn mẹtala tí wọ́n ń gba ìtọ́jú ní òpin oṣù kẹrin.Oṣù karun un ọdún 2020 ní ọjọ́ karundinlogun oṣù karun un, Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀-èdè Eritrea fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹni ikokandinlogoji, ti ó tún jẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 tí ó gbẹ̀yìn ní orílẹ̀-èdè Eritrea, ti gba ìwòsàn patapata..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́rìnlélọ́gọ́jọ ni ó ṣẹlẹ̀ nínú oṣù kẹfà, èyí ló mú kí iye àpapọ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ láti ìgbátí àjàkálẹ̀-àrùn yí ti bujáde lọ sókè sí mẹ́tàlénígba..
wikipedia
yo
Awon alaisan metalelaadota ni won gba iwosan ninu osu kefa o wa ku aadojo awon alaisan ti won n gba itoju titi di opin osu kefa.Awon igbese lati dena ajakale-arun COVID-19 lati dena ajakale-arun COVID-19, ijoba ti ro awon ara ilu lati ma se rin irin-ajo lo kuro tabi wa si orile-ede Eritrea..
wikipedia
yo
Awon arinrin ajo ti won n bo wa si orile-ede Eritrea, sugbon ti won ti se abewo si orile-ede China, Italy, Korea guusu tabi iran laipe yi ni ijoba ti ko lo si ibi ifinípamọ́ lati ojo Kọkànlá osu keta odun 2020.lara awon ilana ti ijoba gbe kale ni lati dena gbigbe owo lori awon oja lákòókò isemole..
wikipedia
yo
Awon àmús̩e̩ igbese yi ni won ti kede won ni awon agbegbe bi i massáwa.Bí ajakale-arun yí ṣe n posi, ijoba pinnu lati je ki gbogbo awon omo orile-ede Eritrea wa ni isemole, won si fi ofin de gbogbo irin-ajo awon oko ofurufu, ti won ko se pataki, ti won je ti agbegbe ati ti ilẹ okeere..
wikipedia
yo
Lákòókò tí wọ́n fi òfin de àwọn ìrìn-àjò lọ sí ilẹ̀ òkèèrè, àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Eritrea tí wọ́n ń padà bọ̀ láti ilẹ̀ òkèèrè ni wọ́n kàn án nípa fún láti lọ sí ibi ìfinípamọ́..
wikipedia
yo
Láti ọjọ́ kẹrìndíndínlógún Oṣù Kẹfà, àwọn ènìyàn 3,405 ni wọ́n sì wà níbi ìlómọ́dì ․kiri àwọn ibi ìlórí mẹtadinlaadọta tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ẹritrẹ́à.Àwọn Ìtọ́kasíLọ́wọ́lọ́wọ́
wikipedia
yo
The ajakale arun COVID-19 ni tan kale de orile-ede Mozambique ni aarin osu keta odun 2020.Bi o se bere ni ojo kejila osu kini odun 2020, ajo isokan ti o n ri si ilera ni agbaye fidi arun korona ti a tun n pe ni Kofid-19 ni orile-m agbaye ni ojo kejila osu kinni ni odun 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tó ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé létí .Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ síwájú sí wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, òun ni ó ń fa ìfunpínpín ní ní inú káà ọ̀fun àti àyà, tí ó sì ma ń fa kátà tàbí kí ènìyàn ó má wú ikọ̀ tàbí sìn léra léra..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to àrùn korona látàrí rírán tí ó ń ran kalẹ̀ tí.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lé jẹ́ wípé itankale àrùn COVID-19 ń gbópọn sí lójojúmọ́ tí ó sì ti seku pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lagbaye.</>àwọn àsìkò kọ̀kan tí ó ń ṣẹlẹ̀ kẹta ọdún 2020: Mozambique-èdè ní akosile àkọ́kọ́ ní ọjọ́ kejì Oṣù kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
Wọ́n rí àrùn yí lára ẹnìkan tí ó jẹ́ ẹni ọdún mádínlọ́gọ̀nán tí ó ń darí bọ̀ láti ilẹ̀ United Kingdom..
wikipedia
yo
Ninu osu yi, awon eniyan mejo ni o tun ri ti ayewo si fidi re mule wipe won ni arun àṣekú pani korona.osu kerin odun 2020ni ojo kejo osu kerin odun 2020, won tun ṣàwárí awon eniyan meje miiran ti o ti fara ko Jogbo arun COVID-9 ni orile-ede naa ti o mu ki gbogbo awon ti eọ̀n ti ni arun yi ti je metadinlogun, ni eyi ti awon eniyan mẹ́sàán ko arun naa ran ara won.Ki osu kerin to pari, won ti ri to awon eniyan ti o to mẹ́rìndínlọ́gọ́jọ ti won ni arun korona..
wikipedia
yo
Àwọn méjìlá nínú wọn ni wọ́n rí ìtọ́jú gbà tí ó sì ku àwọn mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ènìyàn tí àìsàn yí sí wa lára wọn.Oṣù Karùún ọdún 2020ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n àti ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Karùún, orílẹ̀-èdè Mozambique pàdánù ènìyàn méjì àkọ́kọ́ sí òwò àrùn COVID-9..
wikipedia
yo
Ní àárín oṣù yí, orílẹ̀-èdè Mozambique ti ní àkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí ó tó ọgọ́rùún kan ó lé méjìdínlọ́gọ́rin, èyí mú kí iye àwọn tí wọ́n ti ní àrùn náà lápapọ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ó jẹ́ ọgọ́rùún méjì ó le Meriléláàdọ́ta..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn 91 ni wọ́n rí ìtọ́jú tí ara wọn sì yá tí wọ́n padà sí ilẹ̀ wọn..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni kò kú nínú oṣù yí yàtọ̀ sí àwọn tí wọ́n ti kọ́kọ́ kú tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Tí àwọn ọgọ́rùún kan ó le mọ́kànlélélé ènìyàn tí àìsàn yí sì wà lára wọn..
wikipedia
yo
<osu kefa odun 2020iyalẹnu ni o je bi iye awon ti arun naa tun kọlù je ilọpo eniyan ti o ti mu tele ninu osu Kárùún pelu awon eniyan Merilélógójì ni ojo ketala osu Kárùún nikan..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹrinla, wọ́n pàdánù enika tí ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìnléléláàdọ́ tí ó jẹ́ ọmọ agbègbè Nam. Province.After celebrate may with 254 confirmed cases, the number of confirmed cases had doubled by 13 June, with a further 44 cases confirmed on that day alone.Àwọn mẹfa ni ó papò dà nínú oṣù kẹfà nígbà tí àwọn ọgọ́rùún méjì ó lé mejilelọgbọn rí ìwòsàn gbà..
wikipedia
yo
Iye awon eniyan ti aisan yi si wa lara won je ọgọ́rùún mefa ati mejilelaadọta.ààtò awon ajakayemed casesmed New casesetun le wo COVID-19 tòótọ́ in Africa COVID-19 tòótọ́ by Country and territoryawon itọkasi ajakale arun COVID-9coronavirus ManaseMozambiqueMozambiqueMozambique outbreaks in Mozambique..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn run COVID-9 wọ orílẹ̀-èdè Zambia ní inú oṣù kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
bi o ṣe bẹrẹ ni ojo kejila osu kini odun 2020, ajo isokan ti o n ri si ilera ni agbaye fidi arun korona ti a tun n pe ni Kofid-19 ni orile-ede agbaye ni ojo kejila osu kinni ni odun 2020..
wikipedia
yo
Iye ijamba ti arun korona ti fa lagbaye kere si iye ijamba ti aisan arun ọ̀fun SARS ti fa lati odun 2003.Amo iye awon eniyan ti won to arun korona latari rírán ti o n ran kale ti.Po ju ti SARS lọ, bi o ti le je wipe itankale arun COVID-19 n gbópọn si lójojúmọ́ ti o si ti seku pa opolopo eniyan lagbaye.Awon asiko kookan ti o n sele keta odun 2020 ni ojo ketadinlogun osu keta, ijoba orile-ede kan ti ti gbogbo ile-eko lati obere de ibi ti o de, ti won si ti fi awon aala ori kookan si irin-ajo awon arin-ajo ti o fe wole si orile-ede won lati awon oloye-ede ilu okere tabi jade kuro...
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè nZambia ni akosile arun COVID-9 meji akoko lara awon olugbe meji ti won je toko-taya ni ilu Lusaka ni ojo kejidinlogun osu keta odun 2020.Won tun ri awon eniyan mejilelogun ti o ni arun korona leyin ti won dari irin-ajo lati orile-ede Pakistan..
wikipedia
yo
Ni ojo karundinlogbon osu keta, Aare orile-ede ZAMBIA Ogbeni Edgar Lundagu fidi awon eniyan mejila miiran ti won tun ni arun korona mule nigba ti o n ba awon omo orile-ede re soro.ninu osu keta, awon eniyan mẹrindinlogoji ti won ni arun korona.osu kerin odun 2020 orile-ede Zambia kede iku shey korona akoko ni ojo keji osu kerin odun 2020.Lapapọ, awon eniyan ogoje ni won bere fun ti won si fidi re mule wipe won ni arun korona ninu osu yi, ti o mu ki iye awon aworan naa lapapo o je mefacats nigba ti awon meta se alaisi..
wikipedia
yo
Awon ti o ku ti won ko ku ti won ko si II ri iwosan gba je mejidinlaadọta ninu osu kerin.osu karùún odun 2020 ni ojo karùún osu karùún, elomiran naa tun papo da ti o mu ki iye awon shey arun COVID-9.Nigba ti o fi maa di ojo kejilelogun osu Karùún, iye awon ti won ti ni arun korona ti di Àádọ́saan o le ogun..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹtadinlọgbọn, Zambia ti ní àkọsílẹ̀ tí ó ti tó ọgọ́rùún kan àti mẹ́tàlélọ́gbọ̀n láàrín ọjọ́ maruun..
wikipedia
yo
tí ó mú kí gbogbo rẹ̀ ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àti mẹ́tàdínlọ́gọ́ta..
wikipedia
yo
Simon miti naa fẹnu si wipe ọgọ́rùún mẹrin ati mẹtalelogoji ènìyàn ni o ti ri iwosan gba ti won si ti pada si ile won..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn méje papopọ̀ dá tí àwọn ọgọ́rùún méjì àti mọkan576 sí ní àìsàn COVID-9 ní ìparí oṣù karùún.Oṣù kẹfà ọdún 2020 ní Ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n Oṣù kẹfà, ìjọba orílẹ̀-èdè ZAMBIA buwọ́ lu iye owó tí ó tó bilionu mẹ́jọ Kwacha (US$439 million) owó ilẹ̀ ZAMBIA, láti fi ṣúase tu àwọn 9mo orile-ede ZAMBIA lára.Iye àwọn ènìyàn tí wọ́n to 437 ní wọ́n tún ṣàwárí wọn nínú oṣù yí, àwọn alaárẹ̀̀ mẹ́rìnlélógún ni wọ́n papò dá, ní ìparí Oṣù kẹfà.ipa tí ajakalè àrùn COVID-9 kọ́ nípa ètò-ẹnubodè COVID Oṣù kẹta kẹta, ìjọba orílẹ̀-èdè ZAMBIA kede wípé kí ó ti gbogbo ilé ilé-ẹ̀kọ́ tàbí gbogbo ijo Jimọ Oṣù ìlú kẹta. Ó igbohunsafefe ilẹ̀ ZAMBIA (z) tí ó David Membà Bó ń ṣṣ fún Kéde ilé-iṣẹ́ náà máa dá ọgbẹ́ kan tí yóò wà fún pẹ̀lú kọ̀mọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀kọ́ ní àsìkò-lẹ̀-mọ́, lati economy-ẹ̀ lati ìdági-ẹ̀-9..9..
wikipedia
yo
ìkànì náà yóó sì bẹ̀rẹ̀e iṣẹ́ ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kẹrin ọdún 2020..
wikipedia
yo
Ogbeni Memba tun fi kun wipe awon yoo pese ilana ikẹkọ miiran fun Ọ̀gọ̀rọ̀ awọn eniyan ti won ko ni anfani lati lo ero amóhùn-máwòrán..
wikipedia
yo
Ijoba yoo tun maa lo ero asọ̀rọ̀-mágbèsì, ẹ̀rọ ayelujara lati le je ki awon oun were o le ni anfani si eto eko-ẹfọ naa.pípaṣẹ waàwọn fẹ̀ṣùn kan awon alaṣẹ ijoba ZAMBIA wipe won n lo ìbúrẹ́kẹ́ ajakale arun COVID-9 lati fi so ara won di ijoba apàṣẹ waa, nipa lílòdì si Ofin Ijoba Ile ZAMBIA ti o so orile-ede ZAMBIA di orile-ede oloselu ijoba awa-ara wa by bi ijoba se fagile ìjókòó awon igbimo asofin ti o ye ki won se ayipada si ofin ti yoo fese ijoba awa arawa mule ṣinṣin , ati bi ijoba se ti ile-ise amo-máwòrán ti o je ti aladani ti ko fi anfani sile fun Pípolongo nipa ajakale arun COVID-9 lọ́fẹ̀.Ẹ tun le wo COVID-19 ] Greek in Africa COVID-19 by 12 and territory sam sam sambi-asa)
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn erankorona (COVID-19) ni won fidi re mule pe o de orile-ede Zimbabwe ni osu keta odun 2020..
wikipedia
yo
Awoon agbegbe ti o wa ni orile-ede Zimbabwe, ni pataki awon bi i Manicaland, Masvingo ati Masholand ti o wa ni ila-oorun orile-ede Zimbabwe paapa ti n tiraka pelu ibujade arun iba kan ti o n sele ni akoko kanna..
wikipedia
yo
Biotile je wipe arun iba je arun ti o se e wo, eto ilera n dojuko aito oogun eyi ti o fa ki igààrà ma a posi pelu bi ajakale-arun COVID-19 se n tan kale.Ipinle ni ojo kejila osu kini odun 2020, ajo ilera ni agbaye (World Health Organization) fidi re mule pe kokoro arun erankorona ni o n fa arun ategun ni aarin opo eniyan ni ilu Wuhan ni agbegbe hube, orile-ede China, eyi ti won jabo re fun ajo ilera ni agbaye ni ọjọ́ọ́ kokanlelogbon osu kejila odun 2019.Ìṣẹ̀lẹ̀ arun COVID-19 kere pupo si ti arun SARS ti o sele ni odun 2003 sugbon bi arun COVID-19 se n tan kíkàwé po pupo, ni pataki ti a ba wo iye awon ti o ti je alaisi.Awon akoko ti awon isele yi n sele keta odun 2020 ni ojo kokanlelogun osu keta ni orile-ede Zimbabwe kede isele akoko ajakale-arun korona ni orile-ede won..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yí ní ti arákùnrin kan tí ó ń gbé ní Victoria Falls tí ó padà dé láti orílẹ̀-èdè àwọn aláwọ̀ funfun (United Ovce) tí ó sì gba gúùsù ti orílẹ̀-èdè Áfríkà (South Africa) wá sí orílẹ̀-èdè Zimbabwe ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta..
wikipedia
yo
Won ko kede pe enikeni je alaisi gege bi awon iroyin kan ti ṣèèṣì so wipe enikan je alaisi lai mo pe alaisan yi si n tesiwaju lati ya ara re soto ni ile re nibiti o ti n ri apẹẹrẹ iwosan.Ìṣẹ̀lẹ̀ meji miran ni o tun sele ni Harare, orile-ede Zimbabwe ni ojo kokanlelogun osu keta..
wikipedia
yo
Ni ojo ketalelogun osu keta, won fidi re mule pe olokiki akoroyin omo orile-ede Zimbanwe ti oruko re n je Zòróró Makamba ni eni akoko ti o koko je alaisi ni orile-ede Zimbabwe latari ajakale-arun korona.Ni osu keta, eniyan mejo ni ayewo fi han pe won ni arun korona, eniyan kan je alaisi nigba ti awon eniyan meje ti o seku n gba itoju titi di opin osu keta.osu kerin odun 2020 leyin iku arakunrin Zororo, eniyan meji miran lo tun se alaisi ti awon ti o ti ku wa di meta..
wikipedia
yo
Nitori aito awon ohun elo fun ilera, awon onisegun ko iwe fi esun kan ijoba nitori ki won le ni idaabobo ti o peye nigbati won ba n toju awon alaisan ti arun yi n baja..
wikipedia
yo
Ni ojo ketala osu kerin, won kede isele meta omiran eyi ti o mu ki apapo iye isele arun korona ni orile-ede Zimkbabwe di metadinlogun.O kere tan, awon akoroyin marun un ni won ti mu fun esun pe won se akojopo iroyin lori ajakale-arun COVID-19.Ninu osu kerin odun, eniyan merindinlogbon ni ayewo fi han pe won ni arun korona ti eniyan meta si je alaisi ninu un won..
wikipedia
yo
Iye isele ti won ti fidi re mule latigba ti ibujade arun yi ti bere ti di merinlelogbon..
wikipedia
yo
Iye àwọn tí wọ́n ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́ ní òpin Oṣù Kẹrin ti di márùndínlọ́gbọ̀n (èyí tí ó ti lọ sókè pẹ̀lú ida ìṣọ̀tẹ̀ dín mẹ́ta nínú ọgọrun un(257%) láti Oṣù Kẹta.)Oṣù káá ún ọdún 2020 nínú Oṣù Karun un, ènìyàn mẹ́rìnlélógóje(144) ní àyẹ̀wò fi hàn pé wọ́n ní àrùn korona..
wikipedia
yo
Iye àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti fìdí rẹ múlẹ̀ Látìgbà ti ibujade àrùn yí ti bẹ̀rẹ̀ ti di méjìméjì An(178)..
wikipedia
yo
Iye awon ti won n gba itoju lowo ni opin osu karun un je marundinlaadojo(145) (eyi ti o ti lo soke pelu ida 480 ninu ogorun un(480%) lati osu kerin.)osu kefa odun 2020 ni ojo kejila osu kefa, egbe alare idaraya ti kirikétí (Indian National cricket team) kede wipe awon ti fagile irin-ajo won ti won ti gbero pe awon fe se lo si orile-ede Zimbabwe ni osu kejo odun 2020.Minisita fun eto ilera, Ọbadiah Moyo, ni won mu labe ofin nitori esun sise sise lori owo ti o le ni Milionu merin dola owo ile Amerika (US$4million) pelu omo alakoso okunrin, Collins Mnangagwa, eyi ti o ni se pelu rira awon n kan elo fun idaabobo ara eni fun awon osise ilera ni ona aito..
wikipedia
yo
Ni osu kefa, awon eniyan irinwo ati mẹtala(413) ni ayewo fi han pe won ni arun korona eyi ti o mu ki apapo iye awon isele ti won ti fidi re mule lati ìgbátí ibujade arun yi ti bere di 591..
wikipedia
yo
Ni opin osu kefa, awon alaisan 422 ni o n gba itoju lowo, eyi ti o lo soke pelu ida mokanlelaadowaa ninu ogorun un(191%) lati opin osu karun un.osu keje odun 2020 ile-ise olopaa ti kede wipe awon eniyan 105,000 ni awon ti mu fun esun bojú si awon igbese eto ilera lati dekun arun COVID-19 lati osu keta; eleyi I pelu awon egberun un eniyan ti won mu nitori pe won ko wo sise ni ojo kejidinlogun ati ojo kokandinlogun osu keje.Ni ojo kankandilogun osu keje, orile-ede Zimbabwe kede isenimole kónílé o gbele sugbon won gba awon ti won n se ise pataki nikan laaye lati se ise laarin agogo mẹjọ owuro si agogo meta osan..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ẹ̀sùn kan ìjọba pé ìjọba ń lo àǹfààní àjàkálẹ̀-àrùn yí láti fi lòdì sí ìwọ́de tí àwọn kan ń gbèrò láti gúnlẹ̀ lórí ṣiṣẹ́ owó ìlú ìlànàn.Láti ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 2020, orílẹ̀-èdè Zimbabwe kéde ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó tó 2,817 nínú èyí tí ogójì àwọn aláìsàn ti jẹ́ aláìsí..
wikipedia
yo
Apapo iye awon ayewo ti won ti se je 124,194 ninu eyi ti 68,194 ti se ayewo ti o munadoko (Rapid Diagnostic Test)..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun 2,578 ni ó ṣẹ́yọ ní oṣù keje èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ìbújáde àrùn yí lọ sókè sí 3,169..
wikipedia
yo
Iye awon ti won ti je alaisi ti di metadinlaadorin(67)..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan ti di 1,004 o wa ku awon alaisan 2,098 ti won n gba itoju lowo ni opin osu keje.Ni ojo kokandinlogbon osu keje, Minisita fun oro ile, eto ogbin ati igberiko (Minister of lands, Agriculture and Rural Resettlement), perrance Shiri se alaisi latipase arun COVID-19 leyin ojo die ti awako re na ti farako arun yi.osu kejo odun 2020 won jeri si bi isele arun korona se n po si ni ibere osu kejo pelu awon alaisan to ku latipase arun COVID-19 ti won je ilọpo, lati ogoji si ọgọrin laarin ojo kejidinlogbon osu keje ati ojo keta osu kejo.Ni ojo keta osu kejo, marun un ninu awon osise ile-ise bi owo se n wole (Revenue Authority officials) ni orile-ede Zimbabwe ti won wa lati Beitbridge nibi aala pelu orile-ede South Africa ni ayewo fi han pe won ni arun korona..
wikipedia
yo
Eleyí i ló mú kí ilé-iṣẹ́ ìlera àti ìtọ́jú ọmọdé (Ministry of Health and Child Care) gúnlẹ̀ Ṣiṣẹ́ Àyẹ̀wò fún ọ̀pọ̀lọpọ àwọn òṣìṣẹ́ wọn àti síṣe ìmọ́tótó sí àwọn ohun èlò wọn.Àwọn ọ̀nà lati fi dènà àrùn COVID-19 àti àwọn ipa tí àwọn ọ̀nà yí n kó kí ó tó di wípé wọ́n fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 múlẹ̀ rárá ní orílẹ̀-èdè Zimbabwe ni Alakoso Emmerson Mnangagwa ti kọ́kọ́ kéde Àkókò Pàjáwìrì ní orílẹ̀-èdè Zimbabwe tí wọ́n sì dáwọ́ rìnrìn ìrìn-àjò dúró àti fífagilé àwọn ìpéjọpọ̀ nlá..
wikipedia
yo
Oro ti Minisita fun aabo ni orile-ede Zimbabwe, Oppah MuChinGuri, so wipe iṣẹlẹ arun erankorona le je Ìbáwí Ọlọrun lori awon orile-ede alawo funfun fun fifi iya je orile-ede Zimbabwe fa ariyanjiyan.Ni ojo ketalelogun osu keta, alakoso Mnangagwa kede afikun awon ilana miran lati dẹkun arun korona.
wikipedia
yo
Títì Ẹnubodè Orílẹ̀-èdè Zimbabwe pa fún àwọn ìrìn-àjò tí kò bá ṣe pàtàkì ṣùgbọ́n wọ́n yandá àwọn ará ìlú ati àwọn ẹrù tí wọ́n bá ń bọ̀.
wikipedia
yo
titipa awọn ile ọti, awọn ibi ìgbafẹ́ àlè, awọn ibi ere sinima, awọn ibi Ìlúlé inu ọdọ, ati awọn ẹtọ ere idaraya.
wikipedia
yo
Ṣíṣe àbẹ̀wò sí ilé ìwòsàn kò gbọdọ̀ ju èèkàn lọ ní ọjọ́ kan.Ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ìjọba kéde pé orílẹ̀-èdè Zimbabwe yíò lọ fún látibá ọlọ́jọ́ mọ́kànlélógún bẹ̀rẹ̀ láti ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹta títí di ìgbà tí wọn kò ì ti lè kéde..
wikipedia
yo
Agbegbe iwọran ti Vimọ̀ọ́mọ̀ Falls ni won tun ti pa gege bi i arapa awon igbese isenimole orile-ede Zimbabwe ati ti ZAMBIA..
wikipedia
yo
Lára àwọn àgbékalẹ̀ fún isenimole ọlọ́jọ́ mọ́kànlélógún ni wọ́n ti mú rọrùn látàrí bí wọ́n ṣe gba àwọn ilé-ìtajà nlá ńlá láàyè láti tún má a ta ọtí..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù kẹrin, orílẹ̀-èdè Olómìnira Zimbabwe ṣe àjọyọ̀ ológójì ọdún tí wọ́n gba òmìnira lábẹ́ ẹ̀ isenimole fún ìgbà àkọ́kọ́ nínu ìtàn orílẹ̀-èdè Zimbabwe..
wikipedia
yo
Ni akoko isenimole yi, ọ̀kànlénígba awon ibujade arun iba ni won se akosile won, aadọrun(90) ninu won ni won le kápá nigba ti mọ́kànléyo(131) awon eniyan n Ku.ajo imf se isiro pe o se e se ki oro aje orile-ede Zimbabwe jooro pelu ida 7.4% ni odun 2020 nitori abajade isele ajakale-arun korona.ìyanṣẹ́lódì awon osu osise onisegun mu ipalara wa fun dide arun korona ati itoju awon alaisan arun korona ni osu merin akoko ti i odun 2020.Awon itọkasi Zimbabwe..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 jẹ́ kíkọran de orílẹ̀-èdè Seychelles ní Oṣù Kẹta ọdún 2020..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-Èdè Seychelles ní àkọsílẹ̀ àwọn aláárẹ̀ COVID-9 tí iye wọ́n jẹ́ mọ́kànlá ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù Kárùún ọdún 2020.Àwọn àsìkò tí ó ń ṣẹlẹ̀oṣù kẹta ọdún 2020 orílẹ̀-èdè Seychelles kéde àkọsílẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn COVID-9 rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹta lára àwọn ènìyàn méjì tí wọ́n fara kó àrùn yí lára ẹnìkan tí ó ti ní àrùn yí tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Italy ní ọjọ́kú oṣù kẹta, wọ́n ní àkọsílẹ̀ ẹnikẹta tí tí ó kó àrùn náà nígbà tí ó ń bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Netherlands.Àwọn ẹlòmíràn náà tún ní àrùn yí nígbà tí àwọn náà ń darí bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Netherlands yí kan náà.Nígbà tí oṣù náà yóò fi parí, àwọn mẹ́wàá ni àyẹ̀wò rẹ̀ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé wọ́n ti ní àrùn korona ní orílẹ̀-èdè Seychelles tí ẹnikẹ́ni kò sì kú.Oṣù kẹrin ọdún 2020 ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2020, wọ́n ṣe ìtọ́jú àwọn ènìyàn méjì nínú àwọn aláárẹ̀ COVID-9, tí wọ́n sì padà sí ilé wọn láyọ̀. Oṣù kẹrin, àwọn ènìyàn mẹ́rin nínú àwọn aláárẹ̀ COVID-9, ni wọ́n rí ìtọ́jú gbà tí wọ́n sì padà sí ilé wọn láyọ̀..
wikipedia
yo
Ó sì ku àwọn maruun gegbẹ́n tí wọ́n kù tí wọ́n sì wà lórí ààrẹ náà.Oṣù karùún ọdún 2020 ní oṣù karùún, ìjọba orílẹ̀-èdè Seychelles kéde wípé kò sí òràwọ̀ àrùn COVID-9 ní orílẹ̀-èdè náà mọ̀ bí ó ti yọè kí ó kéré mọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí yóò fi di ojo kejidinlogun osu karùún, gbogbo awon alaárẹ̀ naa ti gbadun tan pata pataosu.Oṣù kẹfà odun 2020 ni ojo kejidinlogbon osu kefa, won tun ri akosile awon eniyan miran ti won je alaárẹ̀ COVID-9 ti iye won to mọ́kàndínlọ́gọ́ta, meje miran ni ojo kokandinlogbon ati merin miran ni Sùnjo osu kefa ti o mu ki iye gbogbo won je ogoji lapapo ninu osu kefa nikan..
wikipedia
yo
Iye awon ènìyàn ti won ti ni arun COVID-9 lati ibere je mọkanNítorítí lapapo, ti awon mokanla ti gba itoju ti won si pada si ile won layo..
wikipedia
yo
Ó ku àwọn àádóje ènìyàn tí wọ́n sì ń bá àárẹ̀ náà jà., níparí oṣù kẹfà..
wikipedia
yo
All 70 had previously tested negative in Abidjan or Dakar but positive on Arday in Seychelles.Oṣù keje ọdún 2020 wọ́n tún ní àkọsílẹ̀ mélòó kan tí wọ́n tí ó tó mẹ́tàlá tí ó mú kí gbogbo iye àwọn tí ó ní àrùn yí gùnkè sí mẹ́rìnléláàdọ́fà, tí àwọn mẹ́tàlá sì jẹ́ ará ilẹ̀ òkèrè.Wọn tún rí àìsàn yí lára àwọn ènìyàn mẹ́fà míràn tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Seychelles, tí ó mú iye àwọn aláárẹ̀ náà lápapọ̀ ó jẹ́ ọgọ́rùún..
wikipedia
yo
Iye awon aláárẹ̀ naa ti di mẹ́rìnbáàrùún nigba ti awon mokandinlogoji eniyan si ri iwosan gba níparí osu kefa.igbese ijobaifagile lilo-bíbòni ojo gogoro osu keta odun 2020, ijoba ile Seychelles ti enu ibodè won ni ori omi ati cruise 576..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ Kẹ́sàán Oṣù Kẹta Ọdún 2020, orílẹ̀-èdè Seychelles fagilé ìrìn-àjò àwọn ènìyàn láti lọ sí orílẹ̀-èdè China, South Korea, Italy àti ìran amọ̀ wọ́n fi àyè gba àwọn tí wọ́n bá fẹ́ padà wá sílẹ̀.okùnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ Pápákọ̀ Ọfurufú kan náà ní àrùn yí tí ó mú kí Iye àwọn aláárẹ̀̀ àrù korona ó di mọ́kànlá ní inú inú oṣù kẹrin..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n ṣàkíyèsí èyí ni wọ́n ṣe òfin kónílé-ó-gbélé fún gbogbo ènìyàn àyàfi àwọn òṣìṣẹ́ tí iṣẹ́ wọn ṣe kókó jùlọ..
wikipedia
yo
Òfin yi yoo bẹrẹ iṣẹ ni alẹ Ọjọru Ọjọ Kẹjọ Oṣu Kẹrin ọdun 2020, yoo si wa ni lilo titi di ojo mokanlelogun gbáko..
wikipedia
yo
It opened Again tó Scheduled Traffic on 1 August.Ilé Ìṣèṣè lẹ́yìn tí wọ́n ṣòfin kónílé-ó-gbélé ní ọjọ́ Kẹ́sàán oṣù kẹrin ọdún 2020, ilé-iṣẹ́ tí ó ń mójú tó ilẹ̀ ìṣèṣèwe ń múra láti sí ilé ọ̀hún padà fún àwọn ènìyàn ní ọjọ́ kíní osù kẹfà ọdún 2020, fún èyí orílẹ̀-èdè Seychelles ni yóò jẹ́ orílẹ̀-èdè àkọ́kọ́ tí yóò ṣí ilẹ̀ ìṣèṣèwe fún àwọn ènìyàn lásìkò ìtànkálẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn COVID-9 ní apá àríwá ilẹ̀ Áfíríkà..
wikipedia
yo
Kí gbogbo ilé-iṣẹ́ àti OKÒWÒ ó tó lè bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òòòjọ́ padà, ilé-iṣẹ́ ìjọba tí ó ń rí sí ètò ìlera wọn ní láti ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ìlànà àti ààtò kọ̀ọ̀kan kalẹ̀ láti lè dá àbo bó àwọn òṣìṣẹ́ ilẹ̀ ìṣèjìnà náà àti àwọn olùṣẹ́ ibẹ̀ gbogbo kí wọ́n ma bá má pín àkàn fúnra wọn..
wikipedia
yo
Ṣíṣe ìmọ́tótó Ayika gbogbo, ati itọju oun ìrànwọ́ fun awọn oṣiṣẹ naa.mimu ìdẹ̀rùn ba awọn ofin ni ojo kejidinlọgbọn osu kerin, Aare ile orilẹ-ede Seychelles Ọgbẹni Danny faureure kede wipe ijọba ti setan lati mu ìdẹ̀rùn ba awọn ara ilu lori awọn ofin ti wọn ti ṣe lati le dẹkun itankale ajakale arun COVID-9 ni orile-ede naa..
wikipedia
yo
Wọ́n gbójú kúrò kúnb òfin ìrìnà ní ọjọ́ kẹrin oṣù karùún ọdún 2020, nígbà tí wọ́n tún fàyè gba àwọn ilé-ìtajà gbogbo láti ma bá iṣẹ́ òkòwò wọn lọ ní ọjọ́ yí kan náà láti àárọ̀ títí di agogo mẹ́jọ alẹ́..
wikipedia
yo
Wọ́n sí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo padà ní ọjọ́ kọkànlá àti ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùún..
wikipedia
yo
Wọ́n sì fòpin sí gbogbo àwọn òfin náà ní ọjọ́ kíní oṣù kẹfà ọdún 2020Air Seychelles resumed Domestic flights on May 4, and sei rẹ̀opened to International Traffic on June 1.gbèdéke lórí ìrìn-àjò lọ sókè Òkunni ọjọ́ Kẹ́sà oṣù Karùún, ìjọba orílẹ̀-èdè Seychelles fagilé ìwọlé sí orílẹ̀-èdè wọn láti ẹnu ibodè Victoria títí di ìparí ọdún 2021..
wikipedia
yo
àwọn ènìyàn tí wọ́n bá darí sí orílẹ̀-èdè Seychelles láti orí ọkọ̀ ojú-omi, wọ́n ní láti wà ní iyàrá àdágbé fún òjò fún ọjọ́ mẹ́rìnlá gbáko..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn àwọn tí wọ́n bá darí láti orí ọkọ̀ òfurufú, wọ́n ní láti ṣe àyẹ̀wò láàrín ọjọ́ méjì kí wọ́n tó dá wọ́n sílẹ̀.Ẹ tún lè wo COVID-19 tòótọ́- in Africa COVID-19 tòótọ́ by Country and territoryàwọn ìkayloglosy..
wikipedia
yo
Oloye Bode Akindele (2 June 1933 - 29 June 2020) jẹ onimọran ile-iṣẹ orilẹ-ede Naijiria kan ati Parakoyi ti ilu Ibadanland, ti apapo iye oro re to $ 1.19 bilionu, gẹgẹ bi iwadi ti Ventures Africa se ti won si gbe jade ni ọdun 2013 ninu iwe iroyin Daily Telegraph ..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹni ìkẹrìndínlógún tí ó lówó jùlọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí Buzznigeria tí ṣe àpèjúwe..
wikipedia
yo
Akindele ni oludasile ati Alaga ti Madandola Group, onisowo oju-omi, ile ise ti o n se orisirisi ohun elo, ti olu-ile ise re wa ni United Kingdom.Awon itọkasi awon onisowo ara Naijiria..
wikipedia
yo
Lilian Bola Bach jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré-bìnrin àti Ajiwá ṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbé ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àti ìkẹ́kọ̀ọ́wọn bí Bola tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Lilian ní erékùṣù Èkó..
wikipedia
yo
Yorùbá ni màmá rẹ, ti Bàbá rẹ sin jẹ ọmọ Poland..
wikipedia
yo
Nítorí iṣẹ́ baba rẹ̀, ó gbé ní onírúurú ìlú lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà èwe rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní Army Children's School, ní ìlú Port Harcourt, bẹ́ẹ̀ náà kàwé ní idì Araba Secondary School, ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O kawe gbawẹ ẹri ninu imo iṣe Tiata ni University of Lagos baba rẹ ku nigba ti o wa lọ́mọ ọdun mewaa rẹ gege bi Aji-ṣiṣe ati ise Tiata di gbajumọ afẹ̀wa-ṣiṣe awọn ọdun ọdun ònkà 1990..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn adíje àwọn Omidan tó rẹwà jùlọ ní Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà ló kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìpolówó Ọjà lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn, èyí ló sọ ọ́ di Delta..
wikipedia
yo
LỌ́DÚN 1997 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò, tí ó sin kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì ní Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oloye Gabriel Oruru ìgbíneèdì (ọjọ́ìbí September 11, 1934) ni oníṣòwò àti Onijoyè ará Nàìjíríà lati ìlú ọ̀kadà ní ìpínlẹ̀ Edo..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 tàn kalẹ̀ de orílẹ̀-èdè ní orílẹ̀-èdè Sierra Leone ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kíní Ọdún 2020, àjọ ìtara tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn korona tí a tún ń pè ní ìlúd-19 ní orílẹ̀-M Àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kínní ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tó ọjọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé létí on 12 January 2020.Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ síwájú sí wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, òun ni ó ń fa ìfunpínpín ní ní inú káà ọ̀fun àti àyà, tí ó sì ma ń fa kátà tàbí kí ènìyàn ó ma wú ikọ̀ tàbí sìn léra léra..
wikipedia
yo