cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó ní kí wọ́n mú àkójọpọ̀ orúkọ yí lọ sí ọ̀dọ̀ Mínísítà fún Ààbò lórí Ilẹ̀ àti Ilẹ̀ láti pé kí ó lè dín àpọ̀jù àwọn ènìyàn tí wọ́n wà nínú ọgbà ẹ̀wọ̀n ní orílẹ̀-èdè Màláwì kù.. | wikipedia | yo |
Àwọn ìgbésẹ̀ míràn tí wọ́n tún gbé ní díndín owó epo ètùtùdá kú àti mímójúkúrò lórí asìnrú tí kì í ṣe ti àwọn arìnrìnàjò láti lè fi ran ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí àwọn arìnrìnàjò lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún mòjúkúrò lórí gbígba owó-orí olùgbé lórí àwọn àjèjì dókítà àti àwọn òṣìṣẹ́ ìlera.. | wikipedia | yo |
Wọ́n pe ẹka tí ó ń rí sí àpò ìṣura láti dín àwọn owó oṣù Ààrẹ, ti Mínísítà àti ti àwọn igbákejì Mínísítà kù ní ìwọ̀n ìdá mẹ́wàá nínú ọgọ́rùn ún fún oṣù mẹ́ta láti lè fi àwọn owó yí kojú àjàkálẹ̀ àrùn erankorona.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀ka tí ó ń pa owó wọlé ní orílẹ̀-èdè Màláwì ni wọ́n sọ fún wípé kí wọ́n sí àpò òṣùnwọ̀n kan fún àwọn tí wọ́n fẹ́ finú fẹ́dọ̀ san owó orí fún oṣù mẹ́fà láti lè tún fi ààyè gba àwọn tí wọ́n ti jẹ gbèsè owó orí láti lè san án.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Sikarika pe àwọn òṣìṣẹ́ lati pe ki wọn ma a gba iṣẹ́ ṣe lọ́wọ́ ara wọn yàtọ̀ si àwọn ti wọn n ṣe iṣẹ́ pàtàkì, ni èròǹgbà àti din iye àwọn òṣìṣẹ́ ti yí ọ ma péjọpọ̀ ni ibi iṣẹ́ ku.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kerinla, Aare mutharika kede isemole Olojo mokanlelogun bẹrẹ lati alẹ Satide, ojo ketadinlogun osu kerin.. | wikipedia | yo |
Nigba ti o di ojo ketadinlogun osu kerin, ile-ẹjọ ti o ga julo ni orile-ede Malawi da ijoba lowo ko fun igba die lori imuse isemole Olojo mokanlelogun ti o fe waye.. | wikipedia | yo |
Idakoko yi wa ni ibamu pẹlu iwe atako ti apapọ awọn ajo ti o n ja fun eto ọmọ eniyan ko.. | wikipedia | yo |
Àríyànjiyàn ti Àjọ ti O n ja fun eto ọmọ eniyan gun le lori ni wipe won nilo awon ofin die si lati le Dáàbò bo awon alaini ati wipe isemole yi yio mu ipalara wa si awujo.itọkasiMalawiMalawi.. | wikipedia | yo |
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè São Tomé àti Príncipe lọ́jọ́ kẹfà Oṣù Kẹrin ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
The first death was recorded on 30 April.Bí ó ṣe bere lọ́jọ́ kejila oṣù kìíní ọdún 2020 ni Àjọ elétò Ìlera Àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pe erankorona, COVID-19, ni o ń fa aisan èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wón jábọ́ rè fun ajo who lọ́jọ́ kokanlelogbon osu kejila ọdún 2019.Iye ijamba ikú àrùn COVID-19 kéré si ti àrùn SARS, severe ACUte 1994pirátory syndrome to be sile lodun 2003, ṣùgbọ́n jíjákale arun naa lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lo iye awon eniyan ti arun naa n pa lápa.. | wikipedia | yo |
Àmọ̀ kan fihàn pé ìdá 95% lọ́è Interval fún ìyàtọ̀ ibi ní São Tomé àti principle kéré jù 1.0 lọlẹ̀ karun-un sí kẹfà, ṣùgbọ́n tí ó ti búrẹ́kẹ́ sí i ní ìwọ̀n 1.Bí àrùn náà ṣe ń búrẹ́kẹ́ sí i lati igba de igba igbà kẹfà Oṣù kérin ọdún 2020 ní orílẹ̀-èdè São-arawa àti Príncipe kede ènìyàn mè àkọ́kọ́ tí wọ́n kó àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè náà on.. | wikipedia | yo |
Àrùn náà pa ẹni àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè náà lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún náà.. | wikipedia | yo |
Ní àsìkò yìí, São Tomé àti Príncipe ni ẹni mẹ́rìndínlógún tí wọ́n ti kó àrùn náà, tí ènìyàn mẹ́rin ti rí ìwòsàn, pẹ̀lú àkọsílẹ̀ ẹnìkan péré tí àrùn náà pa.. | wikipedia | yo |
Ẹni tí àrùn náà pa jẹ́ ọmọ ọdún márùnléláàádọ́ta tí ó ń gbé ní ìlú Canàhgo.. | wikipedia | yo |
Lalu ni iye awon ti arun naa si n se ni akoko naa.Lóṣù karun-un odun 2020, iye awon eniyan tuntun ti won ni arun erankorona kede ede São Tomé ati Príncipe je 279, ti eniyan 9 sin ku, ti apapo awon ti won ni arun naa lórílẹ̀ ede naa jephile, ti apapo iye awon ti arun naa ti pa sin je 10.Eniyan 99 ni won kede re pe won tun ko arun naa lóṣù kefa pelu eni kan ti o tun ku, ti apapo iye awon ti won ni arun naa Àpẹẹrẹgi, pelu iye apapo awon ti won ku je mokanla, 11.Lati dena jijakale arun naa, ijoba orile-ede naa kede oniruuru idaduro awon irin-ajo ati isemole Lolọkan.Àkóbá to se fun eto ọrọ aje nla ni ibèsile arun naa se fun won, nitori pe irin-ajo afe ko ida ogun ninu apapo awon iye osise lorilẹ ede São-Tomé ati Príncipe, o fe.Ẹ je pe pe ibi igba fe lo ti ilẹkun won pa.Awon itọka o Tomé ati Príncipe.. | wikipedia | yo |
Aṣiwèrè KIRI, tí a tún ń mọ̀ sí ogún Èkìtì-parapọ̀ ni ogun abẹ́lé tí ó wáyé láàrín ẹ̀yà Yorùbá fún odidi ọdún mẹ́rìndínlógún gbáko.. | wikipedia | yo |
Ogun yí wáyé laarin ilẹ̀ Ìbàdàn tí ó wà ni apá àríwá ilẹ̀ Yorùbá àti ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà àti gbogbo Èkìtì pátá, tí wọ́n wà ní apá Ìlà-Oòrùn ilẹ̀ Yorùbá.Ohun tí ó fa ogun náà ohun tí ó fa ogun yi ní pàtó ni ìlòdì sí bí ilẹ̀ Ìbàdàn ṣe ń jẹ gàba lé àwọn ìlú Yorùbá tó kú lórí, tí Ìbàdàn sì fẹ́ fi ara rẹ̀ dipò alásè wáá bí ìlú Ọ̀yọ́, bí Ìbàdàn ṣe n tẹ àwọn ọmọ ìyá rẹ̀ yókù lójú mọ́lẹ̀, tí wọ́n sì sọ àwọn ìlú wọ̀nyí di ìlú amọ̀nà.. | wikipedia | yo |
Lára ohun tí ó tú ṣokùnfà ogun yí ni wípé ilẹ̀ Ìbàdàn ń fẹ́ kí gbogbo ilẹ̀ Yorùbá wà ní ìṣọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà lásìkò tí ilẹ̀ Ọ̀yọ́ ń ṣe àkóso àti ìjọba lé ilẹ̀ Yorùbá lórí.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ilẹ̀ Èkìtì ń fẹ́ kí kálukú ó ma se ìjọba ara rẹ̀, àmó ki Ìṣọ̀kan, ìrẹ́pọ̀ àti ìbọ̀wọ̀ fúnra ẹni ó wà nínú ìṣèjọba ìlú kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Èyí ni ó fa èdè àìyedè tí ogun KIRI fi bẹ.sílẹ̀ ní ọdún 1877.ṣíṣubú tí ìlú Ọ̀yọ́ ṣubú gẹ́gẹ́ bí ìlú tí ó ń ṣàkóso ilẹ̀ Yorùbá fún bí odidi ọrùndínlẹ́gbẹ̀ta ọdún tí mú kí gbogbo àwọn ìlú amọ̀nà lábẹ́.ìṣèjọba Ọ̀yọ́ ó di Olómìnira tí wọ́n sì ti ń bá ìṣèjọba ara wọn lọ fún bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún.. | wikipedia | yo |
Púpọ̀.Nínú àwọn ìlú yí náà sì ti wáyàmí débi tí wọ́n lè rọ́pò ìlú Ọ̀yọ́ níbi ìjẹ gàba lé àwọn ìlú mìíràn lórí.. | wikipedia | yo |
Ìbàdàn ti jagun ṣẹ́gun ogun Òṣogbo ni ọdún 1840, wọn si ti jagun ṣẹ́gun ogun Ìjàyè ni ọdún 1862 bákan náà, tí wọ́n sì ti di alágbára gidi bi ti ilẹ̀ Ọ̀yọ́.Nínú ogun yí, ilẹ̀ Ààrẹ ọ̀nà káká ni ó jẹ́ aṣíwájú ogún wọn, tí ọbadákẹ́ làtọọsa jẹ́ balógún.. | wikipedia | yo |
Àwọn Èkìtì-parapọ̀ ni tiwọn ni Fábunmi Òkè-irésétì jẹ́ aṣaju ogun fún, kí ó tó di wípé Saraibi ògeden, tí ó jẹ́ balógún fún ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó bó rọ́pò Fábunmi.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọmọ ogun Èkìtì-parapọ̀ tún lo ọgbọ́n ewé nípa gbígbé koto gìrìwò gba abẹ́ ilẹ̀ láti lè fi ṣe akọlú sí àwọn ọmọ ogun Ìbàdàn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún ṣàmúlò alámì nípa fífi àwọn ènìyàn kan ṣe olófòófó ohun tí ó bá ń lọ tàbí ṣẹlẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ọ̀tá kí wọn lè mọ ọ̀nà tí wọn yóò lò láti rẹ̀burú wọn, ìlú ìlara-mọkìn ni wọ́n fi ṣe ojúkò wọn.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni wọ́n tún lo oríṣiríṣi ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti má fi bá ara wọn sọ̀rọ̀, pàápàá jùlọ nípa lílo ìwọ́hùn àwọn ẹranko oríṣiríṣi láti máa fi bá ara wọn jíròrò kí àwọn ọ̀tá ó má ba gbọ́ tàbí mọ ohun tí wọ́n tàkùrọ̀sọ lé lórí, tí ó sì dúró gẹ́gẹ́ bí ọgbọ́n ewé ojú ogun.Bí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ṣe mú òpin bá aáwọ̀ ogun ogun abẹ́lé yí parí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́sà ọdún 1886.. | wikipedia | yo |
DiDÓPIN ìjà oun Ò̀gùn yí ni ó fún ilé Èkìtì-parapọ̀ ní òmìnira tí wọ́n ti ń pòǹgbẹ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Síbẹ̀, ogun kò tán bẹ́ẹ̀ ni kò wá sópin ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú fún ìgbà pípẹ́, ogun kan tún bẹ́ sílẹ̀ láàrin ilẹ̀ Ìjẹ̀bú àti àwọn Gẹ̀ẹ́sì, kí ó tó di wípé àwọn Gẹ̀ẹ́sì wá borí tí wọ́n sì mú wọn lẹ́rú lábẹ́ àkóso Ọ̀gbẹ́ni Robert Lister ọ̀hún.Àwọn Gẹ̀ẹ́sì sọ apá Gúsù ilẹ̀ Yorùbá di ìlú amọ̀nà fún ìjọba ilẹ̀ biritéènì.. | wikipedia | yo |
A kò rí pàtó iye àwọn tí wọ́n kú nínú ogun KIRI ní àsìkò tí à ń kọ́ nípa ogun yí lọ́wọ́, àmọ́ wọ́n nipé wọn kò pa ọmọdé àti àwọn obìnrin ní àsìkò tí wọ́n ń ja ogun yí lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
A sì tún gbọ́ wípé iye àwọn ọmọ ogun tí wọ́n ja ogun yí lápapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọrúndínlẹ́gbẹ̀ta.Ohun tí ìtàn sọ nípa KIRIwọ́n fún ogun yí ni orúkọ rẹ̀ KIRI látàrí ìró ti kẹ̀kẹ́ àdó olóró tí àwọn ọmọ ogun Èkìtì-parapọ̀ lọ láti fi kojú ọ̀tá wọn lójú ogun, tí ó sì jẹ́ wípé òun ni irú àkókò rẹ̀ tí wọ́n yóò lò láti fi jagun ní ilẹ̀ AduIlẹ̀ ní àsìkò náà.Àwọn ìtọ́kasíọdúnàwọn ogun abẹ́lé Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kọ́kọ́ kéde ibesile ajakale àrùn COVID-19 ní lojoojumọla lórílẹ̀ èdè Spain lọ́pọ̀ kẹta ọdún.Bí àrùn náà ṣe ń jákale lati igba de igbàosu kẹta ọdún 2020arákùnrin kan tí ó rin-ajo lati agbègbè kan tí wọ́n ń pè ní iberian Peninsula lo kó àrùn náà wọ́ lọ́l, agbègbè àwọn ọmọ Adúlá Afrika ní orílẹ̀ èdè Indará.Oṣù kẹrin ọdún 2020̀ tí ó ma fi di ọhìn kerindinlogun Oṣù kérin ọdún 2020, ó ti tó iye ènìyàn lórí pẹ̀lú wọ́n ti kéde wọ́n pe wọ́n kó àrùn COVID-19.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kéde ẹni mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n, 27 tí wọ́n wòsàn, tí ẹni meji péré sin kú.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní Western Sahara ní Oṣù Kẹrin ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Agbegbe ti orile ede Morocco pase de ni Western Sahara nikan ni arun naa wa, ko si ni agbegbe Western Sahara ti sarawi Arab Democratic Republicpase de .bi o se bẹrẹ ojo kejila osu kìíní odun 2020 ni ajo elétò ilera agbaye, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pe erankorona, COVID-19, ni o n fa aisan èémí láàárín awon eniyan kan lagbegbe Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ hubei, lórílẹ̀-ede China, eyi ti won jabo re fun ajo who lọjọ kokanlelogbon osu kejila odun 2019.Iye ijamba iku arun COVID-19 kere si ti arun SARS, severe ACUte respirátory syndrome to be sile lodun 2003, ṣùgbọ rírankale arun po gidigidi, pelu iye awon eniyan ti aisan naa pa.Bí arun naa se n tànkálẹ̀ lati igba de igbaìlú Boujdo€ ni awon awon oṣiṣẹ ajo ile-iṣẹ kan to wa labẹ ajo agbaye ti won n pe ni [United Nations Mission for the refẹrẹn in Western Sahara]] (minur (so) koko kede eni merin ti won ni arun naa lọjọ kerin osu kerin odun 2020.Nigba ti o di ojo Kẹsán-an Osun kerin, minur so tun kede eniyan meji tuntun ti won tun lùgbàdì arun naa da mo ti o mu apapọ iye awon ti won ni arun di mefa di mefa.Awon are COVID-19 gegebi orile-ede.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kọ́kọ́ kéde àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní agbègbè ní agbègbè Cecúta lórílẹ̀ èdè Spain ní oṣù kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe ń jàkalẹ̀ láti ìgbà dé ìgbàoṣù kẹta ọdún 2020arákùnrin kan láti agbègbè kan ní orílẹ̀-èdè Làìbéríà ló dé sí Cecúta pẹ̀lú àmìn àrùn COVID-19 lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2020,tí wọ́n sin gbé e lọ sílé ìwòsàn fún àyẹ̀wò fún ọjọ́ márùn-ún.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn àyẹ̀wò tí wọ́n ṣe fún un lọ́jọ́ kẹtala oṣù kẹta, èsì rẹ̀ fihàn pé ó ti kó àrùn náà.Oṣù kẹrin ọdún 2020lọjọ́ kẹrin Ọ̀ṣun kẹrin, iye àwọn tí wọ́n ti ní àrùn náà ní agbègbè Cecúta jẹ́ mẹ́tàlélọ́gọ́rin (83), mẹ́rìnléláàádọ́rin ni wọ́n wà ní ilé wọn, méjì rí ìwòsàn, méje wà nílé ìwòsàn, tí ènìyàn méjì sìn ṣaláìsí.Odidi ènìyàn ọgọ́rùn-ún ní iye àpapọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n kéde pé wọ́n ti ní àrùn náà lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
ẹni méjìlélógójì ni wọ́n rí ìwòsàn, tí ènìyàn mẹ́rin kú.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kéde àrùn COVID-19 àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè olominira ilẹ̀ Kóńgò lọ́ojo lọ́pọ̀ kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́bí kejìlá Oṣù KÌÍNÍ ọdún 2020 ní Àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (Who) jẹ́rìí pé erankorona, COVID-19, ní ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lọ́pọ̀ Wuhan,ní ìpínlẹ̀I hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jámọ̀ rẹ̀ fún Àjọ Who lọ́rẹ́ Oṣù kejìlá ọdún 2019.Iye ijamba Iku àrùn àrùn COVID-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severeté Patpirá First to be sílẹ̀ sílẹ̀ ilé 2003, ṣùgbọ́n jíjá náà lágbára náà lágbára lọ lọ, pàápàá jù lo iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa papoe ye wo àrùn àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè olominira Benin Origi-sha.. | wikipedia | yo |
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 kókó rápálá wọ Punland, tí ó jẹ́ Ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè Somalia, ṣùgbọ́n tí wọ́n dá dúró lọ́wọ́ ara wọn yàtọ̀ sí Somalia gẹ́gẹ́ bí àwọn àjọ àgbáyé ṣe gbà wọ́n .. | wikipedia | yo |
Apapo iye awon ti won ni arun COVID-19 Punland ojo keji Osun karun-un odun 2020 je mejo, ti eniyan kan pere sin ku, bi o tile je pe awon alaṣẹ ijoba Punland gbagbo iye awon iye awon ti won ni arun naa ju bayii lọ.Titi ojo keji osu karun-un odun 2020, Punland je ẹkun isejoba kan ni orile ede Somalia ti won wa ni ipo keta ninu awon ẹkun isejoba ti arun COVID-19 ti poju, leyin BanaaDir ati ile olominira Somalilandbi arun naa se n jakale lati igba de igbaosu keta odun 2020awon alaṣẹ ijoba Punland koko ko jale lati ti awon ile ijosin awon elesin Musulumi pa nigba ti arun COVID-19 seyo ni awon ẹkun isejoba orile ede Somalia lóṣù keta odun 2020.osu karun-un odun 2020ni osu karun-un odun 2020, opolopo awon Minisita ati awon asopo ti Aare Adamland, said Abdullahi dani ni esi ayewo ti fihan pe won ti ko arun COVID-19.. | wikipedia | yo |
Punland Health Minister JAMA Farah Hassan stated that two Punland government reti had tested positive by May 8, 2020.Lọ́jọ́ kẹfà osù karun-un ọdún 2020 ni Mínísítà eto Oro-aje ti agbègbè ìṣèjọba Punland, Abdullahi Abdi hir kọ́kọ́ kede pe oun ni ojú didunni, èyí tí ó ṣeé se kí ó jẹ́ ọ̀kan lára àmìn arun COVID-19.. | wikipedia | yo |
he sought treatment and was diagnosed with the COVID-19 on May 9, 2020.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ díẹ̀ sẹ́yìn, Hir ti ṣe àbẹ̀wò sí agbègbè kan ní Qardho, tí ẹkun omi jà lásìkò náà, ó ní ìgbàgbọ́ pé ibẹ̀ ni òún ti kó àrùn erankorona.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2020, ilé-iṣẹ́ ijọba lórí eto agbe kede iku minisita ile-ise naa, Ismail Gdìíd pe o papòdà lati owo arun COVID-19.. | wikipedia | yo |
Ggdìíd had inhabicted the coronavirus in Punland, but had been transferred to a hospital in Mogadishu for treatment for several weeks.Ẹ Yabe wo àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè olómìnira Benin Aṣọ-iboju nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn káríayé erankorona ọdún 2019àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kéde àrùn erankorona, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí COVID-19 lórílẹ̀-èdè Guinea lọ́ojo ketala Oṣù kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́ojo kejìlá Oṣù KÌÍNÍ ọdún 2020 ní Àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (Who) jẹ́rìí pé erankorona, COVID-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lọ́lé Wuhan,ní ìpínlẹ̀ hubeI, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jáẹ̀ rẹ̀ fún Àjọ Who lọ́̀ lọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019.Iye ijamba Iku àrùn COVID-19 kéré sí ti àrùn SARS, severe ACtété iyetory syndrome to be sílẹ̀ lọ́dún 2003, ṣùgbọ́n jíjákalẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lo iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa papó ò ṣe ń ja ń ja ń ja ohun 2020 Oṣù Oṣù kẹta ọdún 2020 Oṣù ọdún fihàn pé arakunrin kan, ọmọ orílẹ̀ èdè Belgium, tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ Àjọ Àjọrin, tí ó wá ṣe pẹ̀lú àbẹ̀wò-èdè Guinea ní àrùn COVID-19.. | wikipedia | yo |
Òun ni ẹni àkọ́kọ́ tó ní àrùn náà ní lórílẹ̀-èdè náà.Nígbà tí ó yá, iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ní àrùn náà pọ̀ sí ní ìlọ́po méjì láti mẹ́jọ sí mẹ́rìndínlógún lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2020.Oṣù karùn-uniṣẹlẹ̀ láabi kan ṣẹlẹ̀ lóṣù karùn-ún ní Guinea, àwọn ọlọ́pàá pa àwọn mẹ́fà nínú àwọn afẹ̀hónúhàn níbi tí wọ́n ti ń ṣe àyẹ̀wò ìgbòkègbodò ọkọ̀ ní ìlú Coyah àti Dubká.. | wikipedia | yo |
Agbẹnusọ àwọn ọlọ́pàá, Carlan Kaba wí àwíjàre pé àwọn afẹ̀hónúhàn náà ń Fẹ̀hónú hàn nítorí ṣíṣe àyẹ̀wò ìgbòkègbodò ọkọ̀ àti àwọn ènìyàn láti Le gbégi dínà ìtàn àrùn COVID-19, ṣùgbọ́n àwọn afẹ̀hónúhàn náà tako wọ́n pé èyí kò rí bẹ́ẹ̀, wípé àwọn ǹ ṣe ìwọ́de Ìfẹ̀hónúhàn nítorí owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tí àwọn ọlọ́ọlọ́pàá náà ń gbà lọ́wọ́ àwọn ènìyàn.Ẹ yéyí wo ajakalẹ àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin Aṣọ-iboju Nígbà-iboju nígbà AÀjàkálẹ̀ Kariaye erankoA1 Ọdún 2019 Àìsàn inú afẹ́fẹ́àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Barakat Oyinlọ́mọ Qadrẹ̀ (ọjọ́ 1 May 2003) tàbí baraka oyinlọ́mọ wá jẹ́ oníṣẹ́ àgbà tẹ́nì ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Lọwọlọwọ ohun ni ara Naijiria ti ipo rẹ gajulọ ni ẹka ìdíje awọn obinrin ẹnìkan lori WTA.. | wikipedia | yo |
ohun ni ó wà ní ipò kínní ní Nàíjírìa, ipò 9K ní Afrika àti ipò 969 lágbàáyé nínú Idije àwọn Obìnrin ẹnìkan.Iṣẹ́ káyinrí bẹ̀rẹ̀ sí ní gba tẹnis ní ìgbà tó pé ọmọ-ọdún 4.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bíi Junior, ó dé ipò 173 ní ọjọ́ 17 oṣù keje ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ni ibi idije ITF/Cat Junior Championship 2015 ni Mòrókò, Kadiri fi ara rẹ han gege bii ikan ninu awon agba Tẹnis to darajulọ ni Afrika, won tun fun ni sikoläpu si High performance Center ni Mòrókò.. | wikipedia | yo |
At the 2016 ITF U-18 Championship, Barakat made the quarter-finals.. | wikipedia | yo |
In 2017, defeated Chakira dermane of Togo 6–0, 6–0 to set a Quarter Final Clash with Sophia Bíọláy from France.. | wikipedia | yo |
At National Level, she was chosen to represent Nigeria at the 2016 Africa Junior Tennis Championship.. | wikipedia | yo |
She won the ITF/cat u-16 Championship in Togo.At the 2018 Lagos Open, Barakat defeated Airhunmwunde, 6–1, 6–0 to Oriku for the Second round.. | wikipedia | yo |
In her next game, she lost to Anna Siskovkov and Olùgbo out of the tour.ITF Junior ìràwọ̀les (8–1)Àwọn Ìtọ́kasí Agba Aeniolas Ara Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kéde pé òtilè àrùn COVID-19 be sílẹ̀ lórílẹ̀-èdè Madagascar lọ́pọ̀ kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ kejìlá Oṣù kìíní ọdún 2020 ní àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (Who) jẹ́rìí pé erankorona, COVID-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lọ́è Wuhan,ní ìpínlẹ̀ hubeI, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ́ rẹ̀ fún àjọ Who lọ́̀ rẹ́lọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Iye ìjàmbá ikú àrùn COVID-19 kéré sí ti àrùn SARS, severe ACtété ṣàánútory syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 2003, ṣùgbọ́n jíjákalẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lọ iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀.Àjàkálẹ̀ àrùn náà láti igba dé ìgbàoṣù kẹta ọdún 2020ni olú-ìlú orílẹ̀-èdè Madagascar, Antananarivo ni wọ́n ti kọ́kọ́ kéde àwọn ẹni àkọ́kọ́ mẹ́ta tí ó lùgbàdì àrùn COVID-19 lórílẹ̀ èdè náà lógúnjọ oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Obinrin ni gbogbo wọn.Lóṣù Kẹta náà, odidi ènìyàn mẹ́tàdínlọ́gọ́ta ni wo kéde pé wọ́n ní àrùn náà, gbogbo ló sìn wà ninu àìsàn náà títí oṣù náà fi parí.Oṣù kẹrin ọdún 2020láàárín oṣù kẹrin, Madagascar ti ní odidi ènìyàn mọ́kàndínlọ́gọ́fà, 121 tí wọ́n kéde pé wọ́n ní àrùn COVID-19, ṣùgbọ́n kò sí ẹnì kankan tó kú.Àwọn ènìyàn ọ̀kanléláàádọ́rin (71) ni àpapọ̀ àwọn tuntun tí wọ́n karùn náà ní oṣù kẹrin.. | wikipedia | yo |
ti àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ní àrùn náà ní Madagascar láti ìgbà tí ó ti bẹ́ sílẹ̀ jẹ́ èjìdín-lélọ́gọ́fà, 128.. | wikipedia | yo |
Apapo iye awon ti aisan naa si n ba ja titi di ipari osu kerin je mẹrindinlogoji, eyi ti o je idi ku ida mẹtadinlogoji (37%) lati osu keta.osu karun-un odun 2020lóṣù karun-un, Madagascar kede apapo eniyan ti iye won je okandínlógóje (149) ti won ni arun COVID-19 sugbon ko si enikeni to ku.. | wikipedia | yo |
Ẹni àkọ́kọ́ tí àìsàn náà pa ni wọ́n kéde lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù karùn-ún.. | wikipedia | yo |
Òkú náà tí wọ́n kó dárúkọ rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta (57) tí ó ti ní àrùn ìtọ̀ ṣúgà àti ẹ̀jẹ̀ ruru.Nínú oṣù yìí, ènìyàn 643 ni èsì àyẹ̀wò ti fihàn pé wọ́n ní àrùn náà.. | wikipedia | yo |
Àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti ní àrùn náà láti ìgbà tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní Madagascar jẹ́ 771.. | wikipedia | yo |
Iye awon eniyan ti aisan naa si n ba ja titi di ipari osu naa je 597, o je eniyan ipele ti won le si i lati osu kerin.. | wikipedia | yo |
Ènìyàn mẹ́fà ni àrùn náà sìn ti pá lóṣù karùn-ún.Oṣù kẹfà ọdún 2020lọjọ́ kejì oṣù kẹfà, àjọ European Centre for Disease Prevention and Control ti kéde ikú ènìyàn mẹ́fà tí àrùn COVID-19 pa ní Madagascar.Àjàkálẹ̀ àrùn náà sọ̀rọ̀ débi pé wọ́n gbà pé ó ṣòro ju ìjàmbá àsìkò iná lọ, débi pé àwọn ènìyàn tí wọ́n máa ń rí oúnjẹ òòjọ́ láti ibi iṣẹ́ ìgbafẹ́ níláti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá oúnjẹ òòjọ́ lọ sínú igbó.Lóṣù náà, àwọn ènìyàn 1443 ní èsì àyẹ̀wò fihàn pé wọ́n kó àrùn COVID-19, èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n ní àrùn náà di 2214 láti ìgbà tí ó ti bẹ́ sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè náà.. | wikipedia | yo |
1200 ni iye àwọn tí àrùn náà sì wà lára wọn títí di ìparí oṣù kẹfà, èyí ju ìlọ́po méjì lọ sí ti iye oṣù karùn-ún.. | wikipedia | yo |
Ti iye awon eniyan ti won ku le si i ni merinla si ogun.Oṣù keje odun 2020lọjọ́ kejila osu keje, apapo iye awon eniyan ti won ti ni arun naa je 4867, eyi ju ìlọ́po meji awon ti won ni arun naa lo ni ipari osu kefa.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ keje oṣù keje, ìjọba wọn tún pàṣẹ isemole tipátipá ní ààrin gbùngbùn orílẹ̀-èdè náà láti lè dẹ́kun àjàkálẹ̀ àrùn náà sí i.Àwọn ọ̀nà ìdènà àrùn náàwọn kéde isemole tipátipá ní ìlú-ńlá méjì.. | wikipedia | yo |
ìjọba kéde lọ́jọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹ́ta pé ìdádúró gbogbo ìrìnnà ọkọ̀ òfuurufú jákèjádò orílẹ̀-èdè náà yóò wáyé fún odidi oṣù kan gbáko, èyí tí yóò bẹ̀rẹ̀ ní ogúnjọ́ oṣù kẹta ọdún 2020.Nítorí rògbòdìyàn yìí, àìsí àwọn arìnrìn-àjò afẹ́ wá sí orílẹ̀ èdè náà fa ìfàsẹ́yìn fún ilé-iṣẹ́ ìjọba tí ó ń rí sí ìrìnnà ìgbafẹ́.. | wikipedia | yo |
Ní àsìkò yìí ilé ìfowópamọ́ àgbà, Central Bank of Madagascar kó ẹgbẹlẹmùkù owó ilé náà, Ariary síta láti tu àwọn ará ìlú lára nítorí rògbòdìyàn àrùn COVID-19.Woye osu kerin ọdún 2020, Ààrẹ orile-ede Madagascar, andry RaJoelina kede egbógi tí wọ́n gbà pé ó ń wo arun COVID-19, tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní COVID organic, ti ilé iṣẹ́ ìwádìí ìjìnlẹ̀, Madagascar Institute of Applied Research (Miarar), ṣe.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe agbo náà láti ara egbògi ẹ̀wẹ́ dóńgóyárò, tí wọ́n ń pè ní Artemi àti àwọn èwe mìíràn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dá àwọn ológun sí ìgboro láti pín àgbò náà fún àwọn ará ìlú.. | wikipedia | yo |
Ọ̀gágun, Colonel Willy ratovonDrainy kéde lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn pé àgbò náà máa ń fún àwọn èròjà ara ní okun sí i.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ wù kí ó rí, àjọ National Academy of Medicine of Madagascar (anamem) fọhùn pé òun kò fara mọ́ ìgbésẹ̀ ìjọba lórí agbo yìí, bẹ́ẹ̀ náà àjọ àgbáyé fún ìléra World Health Organization (WHO) kìlọ̀ pé kò ì tí ì sí ìdánilójú ìwádìí ìjìnlẹ̀ tó fihàn pé agbo, COVID organic lè wo àrùn COVID-19 ti ìjọba orílẹ̀ èdè Madagascar kéde rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àjọ Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Áfíríkà, African Union bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò pẹ̀lú ìjọba orílẹ̀-èdè Madagascar láti ṣe àyẹ̀wò àgbọ́ náà bóyá ó le wo àrùn COVID-19 tàbí bóyá ó ní ìjàmbá kan tí ó lè fà lágọ̀ọ́ ara.Ní àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè náà pẹ̀lú Antananarivo, ìjọba kéde isemole láti ọjọ́ kẹfà sí ogúnjọ́ oṣù kẹfà ọdún 2020 láti dènà àjàkálẹ̀ àrùn náà lọ́nà tó peléke sí i látàrí àwọn ènìyàn tuntun tí wọ́n ń kó àrùn náà.Ẹ yéyí wo àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin Aṣọ-ìbojú nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn káríayé erankorona ọdún 2019 àìsàn inú afẹ́fẹ́àwọn ìtọ́kasígbogaskarkar.. | wikipedia | yo |
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan jẹ́ ọ̀kan lára ìbúrẹ́kẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn korona tí a tún mọ̀ sí KOFId-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Ohun ti o n sokunfa aisan yi ni arun ofun, aya, ati imu ti won n pe ni bi arun korona se wo orile-ede Sudanajo isokan ti o n ri si ilera ni agbaye fidi arun korona ti a tun n pe ni osud-19 ni orile-ede agbaye ni ojo kejila osu kinni ni odun 2020.. | wikipedia | yo |
Tí wọ́n sì fìdí rẹ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń Pw ní ìdéko Wuhan, ní ẹkùn Hubeí ní orílẹ̀-èdè China.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ síwájú sí wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, òun ni ó ń fa ìfunpínpín ní ní inú káà ọ̀fun àti àyà, tí ó sì ma ń fa kátà tàbí kí lóòótọ́ènìyàn]] ó ma wu ikọ̀ tàbí sín léra léra.. | wikipedia | yo |
Iye ijamba ti arun korona ti fa lagbaye kere si iye ijamba ti aisan arun ọ̀fun SARS ti fa lati ọdún 2003.. | wikipedia | yo |
Amo iye awon eniyan ti won to arun korona latari rírán ti o.n ran kale ti.Po ju ti SARS lo.Awon asiko kookan ti o seleosu keta odun 2020ni ojo ketala osu keta, orile-ede Sudan ni akosile korona akoko ni agbegbe Khartoum.. | wikipedia | yo |
Aláìsàn naa ti kokonde orile-ede United Arab EMIRA ṣaaju ki o se alaisi ni ojo kejila osu keta odun 2020.leyin isele yi, orile-ede Sudan nse si fifun awon ero lati ile okere iwe irina osu si awon orile-ede ti arun naa nti po julo, ti o fi mo orile-ede Italy ati orile-ede Íjíbítì ti o je AlamuLẹ̀hìn ti won nitori iberu ajakale arun korona.osu karùún odun 2020nigba ti o di ojo kokandinlogun osu karùún, awon iroyin iku opolopo eniyan latari ìbúrẹ́kẹ́ ajakale arun korona, da iberu-ojo sile ni orile-ede Sudan, bi o tile je wipe igbese ayewo arun aṣekúpani naa mẹ́hẹ.Awon itọkasiSudan.. | wikipedia | yo |
Alberto Angel Fernandez (; Ọjọ́ìbí 2 April 1959) ni oloselu, àti Aorijéró, tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ Ilẹ̀ Argentina láti ọdún 2019.Àwọn Ìtọ́kasí sí araArgentina.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olóṣèlú Zanu-P àti Igbakeji Aare si Ààrẹ Robert Mugabe.Ìtọ́kasí Ara Sìmbábúè.. | wikipedia | yo |
LỌ́JỌ́ kẹrìnlá osu keji odun 2020 ni ajakale arun COVID-19 koko seyo nile Afirika.. | wikipedia | yo |
Orílẹ̀ èdè Íjíbítì ni ó sì ti kọ́kọ́ ṣẹ́yọ, ti àkọ́kọ́ tí ó ṣẹ́yọ lápá ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà ṣẹ́yọ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Pupọ ninu àwọn tí wọ́n kó àrùn náà kó o láti ilẹ̀ òkèèrè ní Europe ati orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, kì í ṣe orílẹ̀-èdè China tí àrùn ti kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ni wọ́n ti kó o.. | wikipedia | yo |
Ìgbàgbọ́ wa pé ìròyìn nípa àjàkálẹ̀ àrùn náà ní Áfíríkà kò fi bẹ́ẹ̀ dunlẹ̀ tó tàbí kúnjú òṣùwọ̀n bí àjàkálẹ̀ àrùn náà ṣe ń jà rànyìnyìn si nítorí àìsí àwọn ohun èròjà ìléra tó péye.Àwọn onímọ̀ kẹ́dùn pé àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 lè ba nǹkan jẹ́ lọ́pọ̀lọpọ̀ ní Áfíríkà nítorí àìsí àwọn irinṣẹ́ àti ètò ìlera tó péye nílẹ̀ náà, wọ́n ní àwọn ìṣòro bí i, àìsí àwọn irinṣẹ́ àti ètò ìlera tó péye, àìlówó tó, àìní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tó péye fún àwọn òṣìṣẹ́ ìlera, àti àìsí àkọsílẹ̀ tó péye fún àmúlò.. | wikipedia | yo |
Kódà, ọ̀wọ́n nǹkan èlò bí i ọ̀sẹ̀, àti omi yóò wọ́n láwọn orílẹ̀-èdè Áfríkà mìíràn.Ọ̀gbẹ́ni Matshidi Moeti ti bùkúna ilera agbaye, World Health Organization sọ wípé òwò fifo àti ẹkún-síra-ẹni láwùjọ lè jẹ́ ìṣòro ní àwọn apá kan ni Afirika.. | wikipedia | yo |
Isedudu le máà ṣee ṣe, ti iṣoro naa tun le buru si i nitori awọn arun bi i, arun iba, arun kogboogun éèdì , ikọ́ fée, ati arun onigbameji.. | wikipedia | yo |
Awọn olùmọ̀ràn sọ pe, sise ayewo le ran awon orile ede Afirika lowo lati se àdínkù isemole ti o le fa iṣoro fun awon onise òòjọ́ ti won gbójúlé ise òòjọ́ lati jẹun ati lati bo ebi ati ara won.. | wikipedia | yo |
Yàtò sí èyí, ó seé se kí àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 fa iyan ní ọpọlọpọ àwọn orilẹ-ede Afirika .. | wikipedia | yo |
Àjọ Àgbáyé, United Nations sọ wípé, bí wọ́n bá tilẹ̀ mójú tó àjàkálẹ̀ àrùn yìí dáadáa, ó kéré jù, àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn bí i mílíọ̀nùmẹ́tàléWùayeògo (1.3 billion) tí wọ́n wá Afirika yóò nílò irinṣẹ́ àyẹ̀wò COVID-19 tí yóò tó mílíọ̀nù mẹ́rìnlélọ́gọ́rin (74), pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogbóọ́n èrò amúnimi lọ́dún 2020.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀, àjọ World Health Organization ti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè Áfíríkà láti dá ibi àyẹ̀wò sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ sọ wípé, ìmọ̀ nípa ṣíṣẹ́gun àrùn Ebola ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀pọ̀ orílẹ̀ èdè láti gbáradì fún COVID-19 Experts say that experience. ketala osu karun-un ọdún 2020, Lesotho jẹ́ orílẹ̀-èdè Áfíríkà tí ó kéde ẹni tí ó ní àrùn COVID-19 kẹ́yìn; kò sí ìkéde àrùn náà ní agbègbè British Indian Ocean territory, French Southern Territorieslọ àti Saint Helena. _*kerindinlogbon, ó ti ju ìdajì àwọn orílẹ̀ èdè Áfíríkà ti jíjàkalẹ̀ àrùn yìí tí rápálá ràn láàárín ìlú, Lóòótọ́, kò fi bẹ́ẹ̀ sí àǹfààní láti ṣe àyẹ̀wò fún àwọn ènìyàn dáadáa.lose keji oṣù kẹfà,àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n ti kó àrùn COVID-19 ní Afirika ti ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba (200,000) lọ.. | wikipedia | yo |