cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ tún ń ṣegbìnyanjú lọ́wọ́ lọ́wọ́ láti gbé abẹ́rẹ́ àjẹsára sintètìtì jáde nípasẹ̀ àtúnṣe ètò àwọn kòkòrò tí ó ń fa àìsàn àti àrùn..
wikipedia
yo
Èyí yóò ṣe iro tó kí àwọn ìrú wẹẹrẹ ó bẹ̀rẹ̀ sí ń gbáanlọ́wọ́ láti dènà bí àwọn kòkòrò wọ̀nyí ṣe ń lágbára ju àwọn abẹ́rẹ́ ìdá lọ lọpọ̀ ìgbà.àwọn Ìtọ́kasíleraàwọn ìmọ̀ nípa COVID-19 tí ó ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Awon isele ijamba ti o waye latipase ajakale arun korona ti odun 2019–2020 ti nipa rẹpẹtẹ lori agbèègbè ati boju ojo se ri..
wikipedia
yo
ìdínkù nínú àwọn ìrìn àjò ojú òfuurufú ti mú kí àwọn ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ dínkù gan-an..
wikipedia
yo
Isepe ati awọn ilana miiran ti wọn ṣàmúlò ni ìlú China ti yorisi idinku mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ninu ọgọrun-un kabóo to n jade..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn onímọ̀ sáyẹ́ńsì tó ń rí sí ètò ilé-ayé ṣe àlàyé pé ìgbésẹ̀ yìí á fi ẹ̀mí tó ń lò bíi ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀tàdínlọ́gọ́rin pamọ́ láàrín oṣù méjì àti jù bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn náà ti mú ìdíwọ́ bá akitiyan àwọn tó ń rí sí ìpẹ̀sẹ̀ ÀYÍKÁ tó jọjú, ó sì tún fa ìsúnsíwájú ìjọ ti United Nations Clímate Change fún ọdún 2020..
wikipedia
yo
ìdínkù nínú ètò ọrọ̀-ajé tí ó wáyé látipasẹ̀ Idadúró lágbàáyé ti wà ní àsọtẹ́lẹ̀ pé yóò fà súnkẹrẹfà nínú ìdókòwò tí àwọn ilé-iṣẹ́ ti ń pèsè agbára.Ìpilẹ̀ di ọdún 2020, pípọ̀ àwọn èéfín tó ń jáde ní ilé-iṣẹ́ Greenhouse ti yọrí sí ìdìde nínú ìwọ̀n òtútù lágbàáyé..
wikipedia
yo
Iṣẹ awọn eeyan naa fa ibaje ayika lóríṣiríṣi.ṣaaju ajakalẹ arun naa, awọn igbesẹ ti o wa nile ti a si ni lati fi lọ awon elétò ilera bi a ba ni iṣoro ajakalẹ arun ni adiramole ati Jna sira eni..
wikipedia
yo
Àríyànjiyàn ta laarin awon olùṣèwádìí latari pe bi eto oro-aje ba lole die, abajade re yoo fa idinku ninu global Warming, idoti afefe ati omi ti a si mu ki agbegbe wa lalaafia.Idoti afẹfẹlatari ipa ti itankale arun korona ni lori irin ajo ati ile-ise, idoti afefe ti dinku ni awon agbegbe kan..
wikipedia
yo
ìdínkù nínú ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ lè mú ìdínkù bá Clímate Change àti àwọn ẹ̀wù tó wà nínú ìtànkálẹ̀ àrùn náà..
wikipedia
yo
Àmọ́ kò ì sí ìdánilójú irúfẹ́ ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ tó wọ́pọ̀ sí ẹ̀wù inú Climate Change àti COVID-19.Àjọ tó ń rí sí ṣíṣe ìwádìí lórí Ìpèsè Iná àti ìmọ́tótó afẹ́fẹ́ ti sọ ọ́ di mímọ̀ pé àwọn ọ̀nà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn náà bíi ìsẹ́raẹnimọ́lẹ̀ àti ìdíwọ́ nínú ìrìn àjò ti yọrí sí ìdínkù ìdá mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn-ún èéfín kábòónu ti ìlú China ń gbé jáde.Ní oṣù àkọ́kọ́ tí gbogbo ilé wà ní títì pa, ìlú China ṣe àgbéjáde ìdiwọ̀n tó tó igba miliọọnu ton kábòónu ju èyí tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2019 láti ìdínkù nínú súnkẹrẹwó ojú òfuurufú, àtúnṣe epo rọ̀bì àti èédú..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn onímọ̀ sáyẹ́ńsì tó ń rí sí ètò ilé-ayé ṣàlàyé pé ìdínkù yìí a gba ẹ̀mí àwọn èèyàn tó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀tàdínlọ́gọ́rin là.Síbẹ̀síbẹ̀, Sarah ladisLaw láti àjọ strategic and International Studies ṣe àríyànjiyàn pé a ò gbọdọ̀ rí ìdínkù nínú àwọn èéfín yìí gẹ́gẹ́ bí àǹfààní nítorí ìgbìyànjú ìlú China láti mú kí ìdàgbàsókè dé bá ètò ọrọ̀-ajé àti ìṣòwò wọn lè yọrí sí ìjàmbá tó máa le ju tàtẹ̀yìnwá lọ.Láàrin ọjọ́ kìíní oṣù kìíní sí ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹta ọdún 2020, European Space Agency ṣàkíyèsí pé ìdínkù dé bá èéfin Niususus oxide láti ara ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, àwọn ẹ̀rọ amúnáwá àti ilé-iṣẹ́ ní agbègbè pọ̀ Valley ní apá àríwá Italy..
wikipedia
yo
ìdínkù yìí wáyé lákòókò tí gbogbo ilé àti ilé-iṣẹ́ wà ní títì pa lágbègbè náà..
wikipedia
yo
NASA àti ESA tí ń sámójútó ìdínkù àwọn èéfín wọ̀nyí nítorí tí àjàkálẹ̀ àrùn náà kọ́kọ́ wáyé ní ìlú China..
wikipedia
yo
sunkẹrẹfa ninu eto ọrọ-aje latari ajakalẹ arun naa fa idinku ninu idoti ni awọn agbegbe kan paapaa ni Wuhan ni Ilu China..
wikipedia
yo
Ìdinkún náà wo ìdá mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn-ún..
wikipedia
yo
NASA lo irinṣẹ́ kan tí a mọ̀ sí Ozone Látinú Inment (Omi) láti túnppalẹ̀ àti láti ṣàkíyèsí Ozone Likun àti àwọn ìdọ̀tí tó ń ba agbègbè jẹ́ bíi No2, Aerols àti àwọn mìíràn..
wikipedia
yo
Irinṣẹ́ yìí ran NASA lọ́wọ́ láti ṣàmójútó àti láti ṣetúnmọ́ àwọn èsì tó ń wọlé látàrí itipa lágbàáyé.Àwọn ọ̀nà omi àti àwọn nǹkan ẹlẹ́mìí inú omilátàrí àjàkálẹ̀ àrùn náà, ìdínkù ti dé bá ẹja títà àti iye tó ń tà á[19], èyí sì mú kí àwọn ẹja inú omi ó máa ṣegbádùn ara wọn..
wikipedia
yo
Rainer frojíẹsẹ̀ ti sọ ọ́ di mímọ̀ pé àwọn ẹja inú omi yóò tóbi sí nítorí ìdínkù ti dé bá ẹja pípa..
wikipedia
yo
Ó sì ṣàlàyé pé nínú omi Europe, àwọn ẹja bíi herring lè di ìlọ́po méjì nínú òṣùwọ̀n.Ìwádìí àti ìdàgbàsókèbí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdínkù fún ìgbà díẹ̀ wáyé ní ti èéfín kábòdẹ́ káàkiri àgbáyé, International Energy Agency ṣe ìkìlọ̀ pé wàhálà tó dé bá ètò ọrọ̀-ajé látàrí àjàkálẹ̀ àrùn náà lè fa ìdíwọ́ tàbí ìdádúró àwọn ilé-iṣẹ́ tó fẹ́ dókòwò pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ Green Energy..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀, Afagun àkókò ìyàsọ́tọ̀ ti mú kí àwọn iṣẹ́ ọnà jíjìn gbọ́rọ̀ sí..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí àbájáde àìmọ́ tẹ́lẹ̀, àwọn aṣọ ìbòjú tí àwọn èèyàn ń sọ sílẹ̀ káàkiri ń dákún ìṣòro ìdọ̀tí àyíká..
wikipedia
yo
European Centre for Medium-range weather foribùdó (ECMWf) ṣe ìkéde pé idinku tí ó dé ba irin ajo ojú òkòrí lè mú kí àwọn àǹdẹ ojú ọjọ́ tóṣẹ́..
wikipedia
yo
Èyí sì wáyé nítorí ìlò Aircraft Bíọ̀rọ̀Loìrépé Data relay (Amdar) fún ìṣọwọ́, èyí sì jẹ́ irinṣẹ́ kan tó gbòógì láti rí pé àwọn àfojúsùn ojú ọjọ́ tọ̀nà..
wikipedia
yo
Àjọ EcMWf ṣe àsọtẹ́lẹ̀ pé Èsì àwọn Amdar máa dìkú pẹ̀lú ìdá márùn-úndínláàádọ́rin tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ látàrí ìdinkun tí ó dé bá lílò ọkọ̀ òfuurufú.Òṣèlú àrùn náà ti fa ìsúnsíwájú àpéjọ ti 2020 United Nations Climate Change Conference lẹ́yìn tí wọ́n sọ ibi tí àpéjọ náà á ti wáyé di ilé-ìwòsàn..
wikipedia
yo
Àpéjọ yìí ṣe pàtàkì gan-an nítorí Àjọ Àgbáyé ti ṣètò láti gba Aba orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan kalẹ̀ fún Paris agreement..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn náà mú ìdíwọ́ bá fífi èrò orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan han nítorí ọ̀rọ̀ àrùn náà ni gbogbo orílẹ̀-èdè ń gbọ́..
wikipedia
yo
Ìwé ìròyìn Times Magazine sọ ọ́ di mímọ̀ pé èrò láti tún ètò ọrọ̀-ajé lágbàáyé bẹ̀rẹ̀ tún lè fa àfikún àwọn èéfín kàbóonu..
wikipedia
yo
Àmọ́ olùdarí fún International Energy Agency ṣàlàyé pé idinku nínú iye owó epo rọ̀bì lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn náà lè jẹ́ ànfààní ńlá láti dẹ́kun ṣíṣe ìrànlọ́wọ́ lórí ọ̀rọ̀ epo ìga.Ipa ààtúnṣe àwọn àsọtẹ́lẹ̀irebẹ̀rẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ tó ń pèsè gaà àti àwọn ọkọ ìrìnà ni a rí gẹ́gẹ́ bí ìsẹ̀lẹ̀ tó máa mú kí ó gaà àá sí.àwọn Ìtọ́kasíàwọn ìmọ̀ nípa COVID-19 tí ó ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Ọlọjé jẹ́ kòkòrò kékeré tí a kò lè rí pẹ̀lú ojú lásán tó sì lè fa àìsàn tàbí àárẹ̀ sára èèyàn..
wikipedia
yo
A tún máa ń pè é ní kọ́kọ́rọ́ tàbí Aron kékeré nítorí ara olùgbàlejò rẹ̀ ló ti máa ń jẹun..
wikipedia
yo
Ọlọjẹ tí ô wọpọ jùlọ ní fáírọ́ọ̀sì àti bakitéríà..
wikipedia
yo
Awon aisan to ma n fa je eyi to le ran ni to si maa n tan ka, COVID-19 si je okan lara irufe aisan bee.Irúfẹ́ awon arun BeÉEyí ti ko fara han ati eyi to fara hanwúnrẹ̀n "infẹ̀sọ̀" je eyi ti a maa n lo lati fi tọka si ohunkohun to le fa arun tabi aisan bo ti le wu ko kere mo ti o si le fara han bi a ba ṣayẹwo..
wikipedia
yo
Èyí sì máa ń dani lórí rú nítorí àwọn onímọ̀ ìṣègùn fi yé wa pé ó ṣe é ṣe kí á rí àwọn ohun tó máa ń fa àìsàn ṣugbọn àìsàn ò ní sí níbẹ̀.A lè pín àwọn infẹ̀sọ̀ tó máa ń fàmì hàn sọ́nà meji, àwọn sì ni èyí tó hàn gédégbé ati èyí tí àyẹ̀wò fínnífínní máa ń fi hàn..
wikipedia
yo
Àwọn Infẹ̀sọ̀ kan wà tó máa ń ṣiṣẹ́ tó sì máa ń ṣaápọn àmọ́ tí kò ní fàmì hàn rárá..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ni a mọ̀ sí subClinical, èyí ni pé kì í fara hàn..
wikipedia
yo
Eléyìí kì í fi bẹ́ẹ̀ ṣiṣẹ́, o kò máa lúgọ sápá kan ni..
wikipedia
yo
Fáírọ́ọ̀sì bíi herpes náà jẹ́ àpẹẹrẹ Larz.A tún lè pín infẹ̀sọ̀ ṣoríkùn àkọ́kọ́ ní èyí tí ó lè tì ó sì burú tí ó sì máa ń fàmì han kíákíá..
wikipedia
yo
Ẹlẹ́ẹ̀kejì ni èyí tó léwu tí àmì rẹ̀ sì máa ń fara hàn díẹ̀díẹ̀, ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni èyí tí ó burú díẹ̀ tí àmì rẹ̀ sì máa ń pé kí ó tó fara hàn..
wikipedia
yo
èyí tó gbẹ̀yìn ni èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ, òhun sì ni ibi tí ínfẹ̀sọ̀ náà ti bẹ̀rẹ̀ tí a sì san lọ gbogbo ara.Ọ̀nà tó ń gbà ránàrùn yìí máa ń ràn látara ẹnìkan sí ẹlòmíràn, oríṣi ọ̀nà sì ni ó máa ń gbà rán..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì gbọdọ̀ mọ̀ nípa àwọn ohun tó sọ́dọ̀ sínú bó ṣe máa ń ran láti lè mọ bí a ṣe le dojú kọ ọ́..
wikipedia
yo
Fáírọ́ọ̀sì àti bakitéríà ni èyí tó wọ́pọ̀ jùlọ.(b)olùgbàlejò ni èèyàn tàbí ẹranko tó gbà á sára.(d) Ọ̀nà àti jáde ni èyí tí arán náà máa ń lò láti fi jáde lára olùgbàlejò rẹ̀.(ẹ́) Ọ̀nà tí ó máa ń gbà láti ràn ni bí aràn náà ṣe máa ń kúrò láti ara ẹnìkan lọ sí ara ẹlòmíràn.(ẹ) agbègbè ní ibi tí aràn náà máa ń gbà tí ó bá kúrò lára ẹnìkan láti lọ sára ẹlòmíràn tó bá gbà á láyè.(f) Ọ̀nà ìgbà wọlé ni ọ̀nà tó máa gbà wo ara ẹlòmíràn.(g) olùgbàlejò ọjọ́ iwájú ni ẹni tó bá máa gbà á láyè láti wọlé.Oríṣi ọ̀nà ni àwọn aràn yìí máa ń gbà ràn láti ara ẹnìkan wo ara ẹlòmíràn..
wikipedia
yo
Ó lè jẹ láti inú oúnjẹ, omi tabi ìfarakanra, àwọn mìíràn sì máa ń wà ninu afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Àwọn èyí tó wà nínú afẹ́fẹ́ ni a máa mẹ́nubà nínú àkọsílẹ̀ yìí.Pàtàkì jùlọ àti Alanakèjì jùlọ àti alagba ó ṣe ní ní kàyéfì pé àrùn kéréje ni ọ̀pọ̀ àwọn kòkòrò yìí máa ń fà..
wikipedia
yo
Ewu tí àrùn máa ń fà dá lórí bí kòkòrò náà ṣe lè fa ìjàmbá tó ati bí olùgbàlejò náà ṣe le sá fún tó..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, ìlera pípé ara olùgbàlejò máa ń fa wàhálà fún kòkòrò tó bá wọlé láti fa àìsàn..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí ni àwọn onímọ̀ ètò ìlera ṣe pín àwọn kòkòrò búburú náà sí èyí tó pàtàkì jùlọ àti èyí tó máa ń lo àǹfààní.Àwọn kòkòrò tó pàtàkì jùlọàwọn kòkòrò yìí ni èyí tó máa ń fa àìsàn látàrí gbígbé ara olùgbàlejò tó bá ní ìlera pípé láti fa àìsàn..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn kòkòrò yìí máa ń ran èèyàn nìkan àmọ́ àwọn àìsàn mìíràn lè wáyé látàrí àwọn kòkòrò mìíràn tó máa ń dá gbé tàbí èyí tó máa ń ran ẹranko àti ohun aláìlẹ́mìí.Àwọn kòkòrò alagbaàwọn wọ̀nyí ni èyí tó máa ń fa àìsàn tó máa ń ràn sára olùgbàlejò rẹ̀ tí kò ní ìlera tó péye tàbí èyí tó wo ara èèyàn tó ṣiṣẹ́ abẹ..
wikipedia
yo
Àwọn kòkòrò yìí máa ń lo anfaani àìlera olùgbàlejò rẹ̀.Infẹ̀sọ̀ tó pàtàkì jùlọ àti èyí tó ṣìkejìinfẹ̀sọ̀ tó pàtàkì jùlọ ni èyí tó jẹ́ gbòngbò àti ìdí àìsàn lágọ̀ ará..
wikipedia
yo
Infẹ̀sọ̀ tò ṣìkejì sí ni àìsàn tó máa ń wáyé látàrí ewu tí èyí tó pàtàkì jùlọ ti dà sílẹ̀.Bó ṣe máa ń rànìjàlọ́pọ̀ ìgbà, a máa ń pe àwọn àìsàn yìí ní àrànmọ́, ìdí abájọ ni pé ó rọrùn láti ran sára ẹlòmíràn yálà nípa ifọwọ́kàn tàbí ohun tó ń jáde lára wọn..
wikipedia
yo
Oríṣi àwọn àìsàn mìíràn tó ní ọ̀nà kan pàtó tó máa ń gbà ràn bí ọ̀nà ìbálòpọ̀ o kì í ṣe àrànmọ́, kò sì nílò kí a ṣe aláìsàn mọ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn àìsàn àrànmọ́ máa ń ràn láti inú afẹ́fẹ́, oúnjẹ tàbí omi tó ti gbàdọ̀tí sára, ẹranko tàbí ìgbà tí kòkòrò bá gé èèyàn jẹ.Àwọn àmìirúfẹ́ àmì tó máa fara hàn ní ṣe pẹ̀lú irú àrùn tó wà ní bẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn àmì mìíràn máa ń ran gbogbo ara bíi àárẹ̀, àìlèjẹun, ara rírù, ìbá, àágùn, òtútù àti ara ríro..
wikipedia
yo
Àwọn àmì kan sì máa ń hàn lápá kan bíi ará ṣíṣú tabi rúdurùdu ni gbogbo ara, ìkọ́ ati ikùn nímú..
wikipedia
yo
Infẹ̀sọ̀ o kì í ṣe nǹkan kan náà pẹ̀lú àwọn àrùn àrànmọ́, ìdí abájọ ni pé àwọn Infẹ̀sọ̀ mìíràn o kì í fa àìsàn sára olùgbàlejò wọn.bakitéríà tàbí fáírọ́ọ̀sìbí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àmì kan náà ni àrùn bakitéríà àti fáírọ́ọ̀sì máa ń ṣàfihàn síbẹ̀ ó nira láti ṣe ìpínyà nínú èyí tó fa àrùn nínú méjèèjì..
wikipedia
yo
Mímọ ìyàtọ̀ ninu mejeeji ṣe pataki, antibiotiìkì o le wo àrùn fáírọ́ọ̀sì sàn bẹẹ o le wo àrùn bakitéríà sàn.Ìtọ́jú àrùn bá wọ àgọ́ ara èèyàn, àwọn òògùn tó máa ń dojúkọ àrùn ni a lè lò láti dín agbára rẹ̀ kù..
wikipedia
yo
Antibiotiìkì le ṣiṣẹ fun bakitéríà amo ko le ṣiṣẹ fun fáírọ́ọ̀sì..
wikipedia
yo
Iṣẹ antibiotiìkì ni lati mu idinku ba pípọ̀ bakitéríà tabi lati pa a patapata.Awon itọkasiilera imo nipa COVID-19 ti o se pataki..
wikipedia
yo
Katja sei: ​ je ògbóǹtagí idaraya ori iluyi, omo orile-ede Russia.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Àìsàn inú afẹ́fẹ́ tàbí atẹ́gùn jẹ́ àìsàn kí àìsàn tí kòkòrò afàìsàn lè fa ti ẹ̀rùn rẹ̀ nínú atẹ́gùn lè ṣàkóbá fún ẹlòmíràn bí wọ́n bá mì í sínú..
wikipedia
yo
Ogún irú àìsàn báyìí ṣe pàtàkì sí ènìyàn àti ẹranko..
wikipedia
yo
Àwọn kòkòrò afàìsàn náà lè jẹ kòkòrò ààrùn-ẹran, bakitéríà, tàbí fọ́nngai tí wọ́n lè ràn káàkiri nípa èémí, ọ̀rọ̀ sísọ, ìkó wúwú, èésin sì sín, pípọ̀ eruku, fífọ́n nǹkan olómi ká, tàbí iṣẹ́ tó bá ń fa ẹ̀rún inú atẹ́gùn tàbí nǹkan tó lè fọ́nká nínú atẹ́gùn..
wikipedia
yo
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, àwọn ẹ̀rún àìsàn ninu atẹ́gùn máa ń fa àrùn láti imú, ọ̀fun, sinuses, ati ìfun, èyí ló máa ń fa ìkọ́, ọgbẹ́ ọ̀fun ati àwọn àmìn àwọn àìsàn míì tó lè ṣẹ́yọ lágọ̀ọ́ ara..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ àwọn àrùn ẹran wọ̀nyí nílò afẹ́fẹ́ àyíká àdáwà nígbà ìtọ́jú.Àgbéyẹ̀wò ẹ̀rùn kòkòrò àìsàn tí atẹ́gùn máa ń fọ́nká ló máa ń fa àwọn àrùn inú atẹ́gùn..
wikipedia
yo
Orísun wọ́n máa ń ṣáásì máa wá láti ara omi ara alárùn ẹran tabi ẹranko, tabi àwọn ìdọ̀tí ohun èlò..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀run àìsàn tí wọn máa n fa ẹ̀yí ni wọn n pè ní kòkòrò afàìsàn..
wikipedia
yo
Wọ́n lè ràn ká nínú afẹ́fẹ́, eruku tàbí omi, tí wọ́n sì lè rìn jìnnà tàbí wà nínú afẹ́fẹ́ fún ìgbà pípẹ́.Fún àpẹẹrẹ, ṣinṣin lè fọ́n àwọn ẹ̀rún àìsàn ká káàkiri inú ọkọ̀ akérò kan..
wikipedia
yo
mímí sínú àwọn ẹ̀rùn àìsàn máa ń ṣáábà fa àìsàn infdmation, èyí sin máa ń ṣàkóbá àwọn ẹ̀yà èémí..
wikipedia
yo
didotì afẹ́fẹ́ kò sí lára àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́ tí ó máa ń ṣe ènìyàn, ṣùgbọ́n dídọ̀tí afẹ́fẹ́ máa ń kópa pàtàkì nínú àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́ tí kò jẹ mọ́ iṣẹ́ ènìyàn bí i ìkó-ke àwọn ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ máa ń ṣàkóbá fún ọ̀fun ènìyàn nípa sísọkúnfà ọ̀pọ̀ àìsàn inú afẹ́fẹ́ ti fgúmation.Àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́ náà lè ṣàkóbá fún àwọn ẹranko..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, Newcastle disease jẹ́ àrùn àwọn ẹyẹ tí ó máa ń ṣe àwọn ẹyẹ ọ̀sìn káàkiri àgbáyé nípa ìdọ̀tí inú afẹ́fẹ́.Ìkórànàwọn àrùn ẹran máa ń já kalẹ̀ nígbà tí alára dídá bá mi ẹ̀rún àìsàn sínú tàbí bí irú ẹ̀rún àìsàn bẹ́ẹ̀ bá bà lé e lójú, lẹ́nu, tàbí imú..
wikipedia
yo
Kò pọn dandan kí alára dídá ènìyàn ní ìfojúkojú pẹ̀lú aláàrùn kí ó tó lè kó àrùn wọ̀nyí..
wikipedia
yo
bí ojú ọjọ́ ṣe rí, nígbà ọjọ́ tàbí ẹ̀rùn, yálà ní ìta gbangba tàbí nínú ilẹ̀ máa ń kópa pàtàkì nínú ìkọràn àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Àwọn nǹkan mìíràn tí ó máa ń ṣokùnfà ìtànkálẹ̀ ẹ̀rùn àìsàn ni ìjì, òjò, àti ìṣe àti ìmọ́tótó ènìyàn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìyàsọ́tọ̀ ètò ojú-ọjọ́, ìwọ́jọpọ̀ àwọn ẹ̀rún-àìsàn Gnngàá nínú afẹ́fẹ́ máa ń dínkù; lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, àwọn ẹ̀rún-àìsàn wọ̀nyí máa ń pósí ní ìlọ́po tó pọ̀ sí i ju ìgbà tí ojú ọjọ́ bá dá geere..
wikipedia
yo
Eto ọrọ aje oun ayika maa n kopa perete ninu ajakalẹ awon aisan inu afefe..
wikipedia
yo
Ní àwọn ìlú ńlá, ríránkalẹ̀ àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́ máa ń pọ̀ pupọ ju ti àwọn abúlé ati àwọn ìlú kéréje lọ..
wikipedia
yo
Alákálẹ̀ àwọn ẹ̀run-afàìsàn Gnngàá máa n wọ́pọ̀ ní àwọn abúlé..
wikipedia
yo
Wíwà ní ìtòsí àwọn odo ńlá lè ṣokùnfà àjàkálẹ̀ àwọn àrùn inú afẹ́fẹ́.Olúdúnmójútó ẹ̀rọ amúlétutù dáadáa tí fa ibẹ̀sílẹ̀ àrùn Legionella Sepmọ́..’
wikipedia
yo
Àìsí ìmójútó tó péye fún àwọn irinṣẹ́ ilé ìwòsàn ló máa ń fa àwọn àìsàn inú afẹ́fẹ́ tó jẹ mọ́ ilẹ̀-ìwọ̀-dènà àwọn ọ̀nà láti dènà àìsàn inú afẹ́fẹ́ ní lílo àwọn ogun-àjẹsára àìsàn kan pàtó, wíwo ìbòjú àti yíyàgò fún ẹnikẹ́ni tí ó bá ti kó àrùn..
wikipedia
yo
Níní àjọṣe pọ̀ pẹ̀lú ènìyàn tàbí ẹranko tí ó bá láàrùn àìsàn inú afẹ́fẹ́ kò ní kí ènìyàn làrùn náà dandan, nítorí kíkó àrùn náà dá lórí bí àwọn èròjà ìlera ara ènìyàn bá ti lágbára tó àti bí mímí sínú àwọn ẹ̀run afàìsàn ti onitọ̀un mi sínú ṣe pọ̀ tó.Nígbà mìíràn, a lè lo àwọn ògùn Antibiotics láti wo àìsàn inú afẹ́fẹ́ bí i pmonic plague.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn onímọ̀ ètò ìlera ti dábàá pé ìmọ́tótó àti ẹkún-síra-ẹni ( èyí tí a tún mọ sí ẹkún-síra-ẹni láwùjọ) jẹ́ ọ̀nà pàtàkì láti dènà ṣe àdínkù rírankalẹ̀ àìsàn inú afẹ́fẹ́..Kò ṣeé ṣe kí ènìyàn ṣe àdínkù ìjàmbá àti kó àìsàn inú afẹ́fẹ́, ṣùgbọ́n ènìyàn lè dènà kíkó àrùn..
wikipedia
yo
Eto ibo fun gbogbo eniyan ṣe eto idibo fun gbogbo ọmọ ilu to je agbalagba, láìkasi ọla, ipawo, Akombabo, ipo láwùjọ, ẹya eniyan, ẹya ede, tabi idina miran.itọkasiẹ̀tọ́ idibo..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà aláìmọ́ (; ) (pipe ni Yoruba bíi kósa) ní ẹ̀ka ẹ̀yà àwọn Bantu to bùdó sí apágugúúsù Afrika àgàgà ní Eastern Cape..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà Xhosa kékeré (Mfengu) tún wà ní Zimbabwe, níbi tí èdè wọn, Isialáró, ti jẹ́ gbígba bíi èdè ọmọ orílẹ̀-èdè.Àwọn ará gúúsù Afrika..
wikipedia
yo
Àyẹ̀wò àìsàn jẹ́ ìgbésẹ̀ tàbí ọ̀nà kan tí àwọn oníṣẹ́ ètò ìlera ma ń gbà láti fìdí òdòdó àrùn tàbí àìsàn múlẹ̀ ní ara ènìyàn tàbí ẹranko kí wọ́n lè mọ irúfẹ́ oògùn tí wọ́n yóò lò sí kí àlãfíà aláárẹ̀ náà ó lè padà sípò..
wikipedia
yo
Àwọn ohun tí wọ́n nílò láti fi ṣe àyẹ̀wò ní ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá àti ìtàn nípa ìlera aláárẹ̀ àti àwọn ẹbí rẹ̀ lápapọ̀.Àyẹ̀wò ma ń dàmú àwọn oníṣẹ́ ìlera, nítorí àwọn àmì, àti àpẹẹrẹ ma ń yàtọ̀ síra wọn ..
wikipedia
yo
Wọ́n lè mọ̀ níoa ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí aláárẹ̀ pẹ̀lú lílo ìlànà ìfọ̀rọ̀ wáni lẹ́nu wò lórí bí ìlera rẹ̀ ti ṣe olùria wa..
wikipedia
yo
Ni pato, Iṣẹọdun aisan nipasẹ ayewo ni awon igbese olokan o jokan ninu.Àyẹ̀wò arun COVID-19won le se ayewo fun arun korona pelu lilo ilana ìṣesí ati apẹẹrẹ ti o fi n hande, amo won ko le fidi re mule boya o wa ninu ago ara aya fi ti won ba lo (r-rt-gi) tabi ct ti o nise pelu àágùn ati awon nkan miiran..
wikipedia
yo
Iwadi kan n lọ lọwọ nipa Isaiwe laarin PCR ati ct ni ilu Wuhan , lori ajakale arun korona..
wikipedia
yo
Àbá tí wón dá ní wípé CT tete ma ń fi ìmọ̀sílara hàn ju pCR lọ..
wikipedia
yo
Ni inu osu keta odun 2020, ike-eko ti redioloji ti o kale si ile Amerika fowo si wipe won ko gbọdọ lo ct fun ayewo akoko fun iwadi nipa arun korona.Àyẹ̀wò fun fáírọ́ọ̀sìajo ilera agbaye (who) fi ilana ati igbese ti awon onise ilera gbọdọ tele lati fi se ayewo ẹjẹ (Flag) fun arun COVID-19, ni ojo ketadinlogun osu kini odun 2020..
wikipedia
yo
Wọ́n ń lo ìlànà àtoríkòdì fún yẹ̀wò nana tí ó jẹ nípánu (rt-ron)..
wikipedia
yo
Àyẹ̀wò yí lè ṣeé ṣe nínú ẹ̀jẹ̀ tí wọ́n gbà sílẹ̀ àti àágùn, itọ́, ikùn, itọ́ tàbí ìgbẹ́ tí ó bá jáde lára ènìyàn..
wikipedia
yo
tí èsì àyẹ̀wò yóò sì jáde láàrín Wálìmati mélòó kan tàbí ọjọ́ péréte..
wikipedia
yo
Lápapọ̀, wọ́n tún má ń ṣe àyẹ̀wò yí lórí àw9ń kẹ̀lẹ̀bẹ̀ ọ̀nà ọ̀fun nítorí ìdíwọ́ tí ó má ń mú bá èémí ní ọ̀fun..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, oúpọ̀ nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tí lórúkọ lágbàáyé tí ń gbé ìgbésẹ̀ lórí bí wọn yóò ṣe ṣẹ̀dá àgbò olómi kan tí yóò ma ṣèwà nípa ìṣesí àwọn kòkòrò àtohun-rin-wà àti àwọn ọmọ ogun ara ìgbà tí wọ́n bá kan ara wọn..
wikipedia
yo
Titi di ojo K3fa osu keje odun 2020, won ko tii ri okan se ni aseyori ninu awon ise iwadi yi ti o le see fi gba arun COVID-19 wole bamu bamu.lara ikan ti agbo wipe Ogbeni Celle se awari re ti awon ajo onise iwadi sẹròlogy fowo si fun lilo ni asiko pajá-ìpàjì ni orile-ede [[Amẹrika). nipasẹ nipasẹ aworan yikas Ìṣesí awon aworan ti o nise pelu ero ayaworan ibi kọ́lọ́fín inu (ct) awon eniyan ti won ni arun korona..
wikipedia
yo
Àwọn Àjọ Ilẹ̀ Ìtaly tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ lórí àwòrán ń gbìyànjú láti ṣe Àkójọ gbogbo Àwòrán àwọn tí wọ́n ti lùgbàdì àrùn korona ní orílẹ̀-èdè àgbáyé..
wikipedia
yo
Àmọ́ ṣá, látàrí bí àwọn àrùn náà ṣe ń gorí ara wọn lásìkò ìbúrẹ́kẹ́ Àjàkáke àrùn COVID-19 àti àrùn Adégananvirus, yíya àwòrán Àwọn gbígba àwòrán àwọn tí wọ́n ti lùgbàdì àrùn pẹ̀lú PCR nira díẹ̀ nítorí iwọ̀-bọnu àwọn àrùn náà..
wikipedia
yo
Wọ́n gbé iṣẹ́ iwadi nla kan ni orílẹ̀-èdè China nípa ìyàtọ̀ ti ó wà ni arin lilo ẹ̀rọ ayàwòrán CT àti PCR, tí wọ́n sì ṣàfihàn yíya aworan àwọn tí wọ́n ti lùgbàdì àìsàn korona kò ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo