cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Miss Grand International jẹ idije ẹwa kariaye fun awọn obinrin alailẹgbẹ.. | wikipedia | yo |
Ti ipilẹṣẹ ni Thaláǹdì ni ọdun 2013.Ni ọdun 2019, keje iru rẹ to waye nilu Caracas tọmọ lọjọ 25, Oṣu Kẹwa, Omidan Valentina Figue, to je aṣoju orilẹede Fẹnẹsúélà lo jawe olubori nibi eto naa.. | wikipedia | yo |
Orílẹ̀-èdè ọgọ́ta ló kópa nínú Ìdíje náà. Àwọn aṣojú àwọn orílẹ̀-èdè tí ó sọ èdè Yorùbá àti Benin kò darapọ̀ mọ́ ìdíje náà.. | wikipedia | yo |
Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ sí kópa nínú ìdíje náà láti ọdún 2014.bọ́tìnì àwọmiss Grand Nàìjíríàfọ́tò ti Miss Grand Naijiriàwọn itọkasiExternal yááfì official website of Miss Grand International Miss Grand International on Facebook Miss Grand International on Instagram Miss Grand International on Twitter Miss Grand International on YouTube aswọn Àgbájọọrọ-okòwò.. | wikipedia | yo |
Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko mejidinlogun, ìkọ̀ọ̀kan wọn ni orúkọ oluilu rẹ̀ àyàfi fún Bujumbura Rural.. | wikipedia | yo |
jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ara Nàìjíríàaitọ́kasíàwọn agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
jẹ agbabọọlu-ẹlẹ́sẹ̀ ara Naijiria,wọn bi Yakubu Aiyegbeni ni ọjọ kejilógún osu Kọkànlá ni 1982itọkasiàwọn agbabọọlu-ẹlẹ́sẹ̀ ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
John Pombe Magufuli (ọjọ́ìbí 29 October 1959), ni olósèlú ará Tànsáníà àti Ààrẹ 5k ilẹ̀ Tànsáníà, lórí àga láti ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
Magufuli tun ni alága Southern African Development Community.Ìtọ́kasíàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Tànsáníà.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan Ilẹ̀ Tànsáníà () ni Olórí Orílẹ̀-èdè àti Olórí Ìjọba Ilẹ̀ Tànsáníà.. | wikipedia | yo |
The President Leads the executive branch of the government of Tanzania and is the commander-in-Chief of the armed forces.See alsotanpisa5BFR of Tanzanijariwafa of governors of Tanganyikalist of heads of state of Tanzaniaprime minister of Tanzanijariwafa of Prime Ministers of Tanzani: of Sultans of ZanzibarPresident of Zanzibarlist of heads of government of Zanzibarlists of INCumbe1977 1964 panáments in Tanzania.. | wikipedia | yo |
Kíbu, tí a mo bakanaa bíi dissatis, ní èdè Bantu tó jẹ́ èdè àwọn ènìyàn mílíọ̀nù 9 ní Burundi àti ní apá Tanzania àti Democratic Republic of the Congo, àti ní Uganda.Ìtọ́kasíàwọn èdè Burundi.. | wikipedia | yo |
Iyán-lódìlódì, tàbí ìfẹ̀hónú han àwọn òṣìṣẹ́ , tàbí ìdágunlá, jẹ́ iyànṣe ni posin tàbí ìdásẹ̀ dúró àwọn òṣìṣẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ ọjọ́ wọn.. | wikipedia | yo |
Iyán-lódìlódì sábà ma ń wáyé láti fi ṣe ìfẹ̀hónú-han àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ tako ìwà, ìgbésẹ̀ tàbí àṣẹ tí kò tẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ lọ́rùn tí àwọn aláṣẹ ilé-iṣẹ́ kan yálà ti ìjọba tàbí àdáni gbé kalẹ̀ fún àwọn òṣìṣẹ́ láti tẹ́lẹ̀ láì mú ìtàpórógan dání.Ìtàn rẹ̀ Ìgbésẹ̀ ìlò Iyánṣe-lòdì bẹ̀rẹ̀ sí ní di irinṣẹ́ ìfẹ̀hónú-hàn lágbàyé nígbà tí ìdàgbà-sókè bédé ṣì ń dé sí àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá nlá, pàá pàá jùlọ àwọn ilé-iṣẹ́ ìwakùsà.. | wikipedia | yo |
Lọ́pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè nígbà náà fòfin de ìyànse-lódì àwọn òṣìṣẹ́ nítorí wọ́n rí iyànse-lódì yí gẹ́gẹ́ bí ohun àìtọ́ sí ètò ọrọ̀-ajé orílẹ̀-èdè wọn, àti nítorí wípé ìjọba tàbí àwọn onílẹ̀ iṣẹ́ aládàáni ní agbára ju àwọn òṣìṣẹ́ lọ.. | wikipedia | yo |
Diẹ lara awọn orilẹ-ede alawọ funfun lo fowo si lilo iyanṣe-lodi awọn oṣiṣẹ lati fi jija-n-gbara lọwọ ìfipá muni ṣe iṣe awọn onise gbogbo ni ipari ọrundu mọkandinlogun (19th or early 20th Centuries).iwulo Iyánse-lodiawọn oṣiṣẹ ma n lo iyanṣe-lodi lati fi yi aṣẹ ati ìpinu awọn agbani-ṣiṣe tabi ijọba pada lori igbese tabi aṣẹ ti wọn ba pa ti ko si ba awọn oṣiṣẹ lara mu.. | wikipedia | yo |
lópò ìgbà, wón ma ń lo iyansé-lòdì láti fi bá ìṣèjọba aláṣe tàbí ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà lórí àléfà lọ́wọ́ jẹ́, bí ìpinu àti ìgbésẹ̀ ìṣèjọba bẹ́ẹ̀ bá tako ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.Àwọn àpẹẹrẹ ìyànsẹ̀-lòdì iyànsẹ̀-lòdì àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ogunìyànṣe-lòdì àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́-elépo róbìtì Nupengi-yanṣẹ́-lòdì àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́ elétò ìlera ti n àti àwọn mìíràn.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ètò ìkànìyàn ni ìgbésẹ̀ kan tí a fi ń ṣe àkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní ìletò, ìlú ìpínlẹ̀ tàbí orílẹ̀-èdè kan nípa kíka àwọn ènìyàn ní orí-ò-jorí ní ojúlé sí ojúlé.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí àjọ àgbáyé ṣe làá kalẹ́, ètò ìkànìyàn gbọ́dọ̀ má wáyé ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan láàrín ọdún mẹ́wàá síra wọn.Ohun tí ètò ìkànìyàn gbọ́dọ̀ kó sínúètò ìkànìyàn gbọ́dọ̀ ṣàfihàn àkọsílẹ̀ iye ọkùnrin, obìnrin, ọmọdé àti àgbà pẹ̀lú iye ọjọ́ orí wọn lásìkò ìkànìyàn.. | wikipedia | yo |
Bakan naa, o gbọdọ se akosile iye ile, ati iye idile ti o wa ninu Ililu tabi ileto ti o wa laarin Ipinle ati orile-ede kookan.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Saint Ann's Bay ní ìlú kan ní Jàmáíkà, ibẹ̀ ni oluilu Saint Ann Paris.. | wikipedia | yo |
Iye àwọn ènìyàn ibẹ̀ tó 13,671 ní ọdún 2009.Floyd Lloyd àti Burning spear _ wọn jẹ́ olórin, àti Marcus Garvey wá láti ibẹ̀.Ìtọ́kasí_*.. | wikipedia | yo |
Ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ tàbí ibani lòpọ̀ lọ́nà àìtọ́ jẹ́ ìfipá múni láti bá ṣe àṣepọ̀ yálà láti ọwọ́ akọ (ọkùnrin)tàbí abo (obìnrin) nígbà tí ẹni tí a fipá mú kọ̀ láti jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún ìbálòpọ̀ lásìkò tí a fẹ́ bá ṣeré lóko-lay.. | wikipedia | yo |
Ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ yí lè wáyé nípa fífi agbára múni tàbí lílo ipò àṣẹ fúni láti báni-lòpọ̀ lọ́nà àìtọ́, nígbà tí ẹni tí a fẹ́ fi agbára mú kó bá ní ọ̀nà tí ó lè fi dáàbò bo ara rẹ̀ lásìkò náà, tàbí kí ẹni tí a fẹ́ hùwà kó tó sì ó kéré jọjọ lọ́jọ́ orí.Àkójọpọ̀ Àkọsílẹ̀ ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ lágbàsùnsùn ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ àti ìfìyà-jẹni lórí ìwà kó tó yí yàtọ̀ sí ara wọn ní orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè ní àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Lápapọ̀, iye àwọn ènìyàn tí a fi ẹ̀sùn ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 2008 jẹ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ìdáunun un (100,000 people), láti 0.2 ni Azerbaijan sí 92.9 ní ìlú Botswana àti 6.3 ní ìlú Lithuania gẹ́gẹ́ bí ìdá méjì (Median) ìṣẹ̀lẹ̀ yí lágbàyé nínú àkójọ àkọsílẹ̀ nípa ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ lágbáyé, ọkùnrin ló sábà ma ń hùwà kó tó yí sí obìnrin jùlọ.Àwọn ìlànà ìfipá báni-lòpọ̀ ìfipá báni-lòpọ̀ láti ọwọ́ àrẹ tàbí àlejò kò fi bẹ́ẹ̀ wọ́pọ̀ nínú àwọn ẹ̀sùn yí, bí kò ṣe láti ọ̀dọ̀ àwọn alábàágbé tàbí aládùúgbò ẹni tí a mọ̀ dára dára.. | wikipedia | yo |
Ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ akọ ṣáko tàbí abo sábó àti ìfipá báni-lòpọ̀ tinú ọgbà ẹ̀wọ̀n náà jé ọ̀kan gbòógì nínú ìlànà ìfipá báni-lòpọ̀ tó wọpọ jùlọ tí wọ́n.Ṣe àkọsílẹ̀ ẹ̀sùn rẹ jùlọ lágbà.Ìwà ìfipá báni-lòpọ̀:ewéewé ní ọ̀nà lílo Ògún àti ìsọni dohun èlò ìbálòpọ̀ (sexual slavery).. | wikipedia | yo |
Àwọn ìlànà wọ̀nyí ló ma ń ṣẹlẹ̀ nígbà tí ogun, ìjà, tàbí ìdàrú-dàpọ̀ bá bẹ́ sílẹ̀ nílú kan tàbí Orílẹ̀-èdè kan.. | wikipedia | yo |
Awon ihuwasi yi láwọn asiko ti a mẹ́nu ba yi ni won n pe ni iwa ọdánran tako o̩mo̩nìyàn (Crime Against Humanity) ati Ọ̀ràn Ogun (War Crime).Ìpalára ti iwa ìfipá bani-lọpọ ma n mu Wapupo eyan ti won ti fipa ba lọpọ le ni ipenija opolo tabi ki won doju ko iṣoro arun opolo leyin isele naa.. | wikipedia | yo |
èwe, ìpalára tó lágbára lè ṣẹlẹ̀ sí ẹni a fipá bá lòpọ̀, lẹ́yìn kí ó lóyún.. | wikipedia | yo |
Àwọn àrùn ìàfojúrí tí a lè kó látara ìbálòpọ̀ lè gbabẹ̀ wọlé sí ẹni náà lára, ẹni a fipá bá lòpọ̀ tún lè má kọjú ìkúkú-làjà láti ọwọ́ ẹni tí ó hùwà àìtọ́ yí síi, tàbí kí àwọn ẹbí ọ̀daràn ó tú má lérí sí ẹni ná pàá pàá jùlọ nínú àṣà ilẹ̀ibòmíràn.Bí a ṣe le dẹ́kun rẹgẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ wípé ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ n kò ìpalára bá wa ní àwọn àwùjọ wa gbogbo, ìjì gírí sí ìdẹkùn ìwà ọ̀daràn yí ṣe pàtàkì.. | wikipedia | yo |
lílà Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Ilé-ẹ̀kọ́ ọlọ́dún mẹ́wàá lọ́yẹ̀ lórí ìpalára rẹ̀, lílà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ àgbà lóyè lórí ìpalára rẹ̀,lílà àwọn òṣìṣẹ́ lọ́yẹ̀ lórí ìpalára rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kòtò dánínú jẹ́ ọ̀nà kan tí a ma ń gbà láti fi yọ́, le, tàbí darí omi tàbí ọ̀gbàrá kúrò níbi tí ó bá ti pònú sí láti ibìkan sí òmíràn.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Efin Alabùkún je oogun ti olóògbé Jacob Soye Odulate ṣàwárí rẹ̀ ní ọdún 1981, lásìkò tí ìmúnisìn àwọn Gẹ̀ẹ́sì ilẹ̀ Britain lágbára gidi.. | wikipedia | yo |
Oògùn yí .Púpọ̀ nínú àwọn èlò oògùn yí ni wọ́n kó jọ láti ìlú Liverpool.Àwọn èròjà inú egbògi náààwọn ohun èlò tí wọ́n fi ṣe egbògi alábùkún oníyẹ̀fun ní acetylsalicylic acid àti caffeine.. | wikipedia | yo |
Àwọn orílẹ̀-èdè bí Nàìjíríà, Benin Cameroon, Ghana àti àwọn agbègbè kọ̀ọ̀kan ní ilẹ̀ Europe náà ni wọ́n tí ń lo egbògi yí.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Abdelmadjid tebboune (; Ọjọ́ìbí 17 November 1945) ni oloselu ara Algeria to je lọwọlọwọ pe ohun ni Ààrẹ ilẹ̀ Algeria lati December 2019.. | wikipedia | yo |
O rọpo Aare AbDelaméje Boutefsirísi ati aropo Olori orile-ede tele Abdelkader Bensalah.. | wikipedia | yo |
teltẹ́lẹ̀, ohun lo jẹ́ Alakoso agba ilẹ̀ Algeria lati May 2017 di August 2017.. | wikipedia | yo |
Bákannáà, ó tún jẹ́ tẹ̀lé Kejì ètò ilẹ̀ láti 2001 di 2002 fún ọdún kan àti ní ẹ̀kán sí láti 2012 di 2017 fún ọdún 5.Ìtọ́kasí ara Algékìllen Ààrẹ ilẹ̀ Algeria.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ orile-ede olominira oselu awon eniyan ile Algeria ni olori orile-ede ati alaṣẹ agba ile Algeria, ati alaṣẹ patapata ile-iṣẹ ologun Algerian People's National armed forces.Ìtọ́kasí Aare ile Algeria.. | wikipedia | yo |
Oloye Jacob Soye Odulate (1884-1962), ti gbogbo eniyan mo si blessed Jacob je omo orile-ede Naijiria Pharmacist, oludasile, alapìlẹ̀ko, onisowoati oludasile egbògi Alabukún.ibẹrẹ aye rea bi Jacob ninu idile olórogún ni ilu Ikorodu, sinu ebi Alagba Odulate ni ipinle Eko ni odun 1884.. | wikipedia | yo |
Bàbá baa re ni Oloye Odukanmade ti o wa lati inu ebi senlu ti o je eka molebi ranOdu ti o je idile oba nilu Imota, ilu ti o sunmo Ikorodu pẹ̀kídin pẹ̀kíd nigba ti o wa ni dédé omo odun merinla, o fese rin lo silu ni ipinle Ogun, ti irin naa si gbaa ni odidi osu meta ki to de Abeokuta.. | wikipedia | yo |
lásìkò tí ó wà ní Abeokuta, ó Poṣ-pàdé onímọ̀ ipò òògùn tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Dókítà sapara, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ṣẹ́ ìmọ̀ ipò òògùn láti ọ̀dọ̀ rẹ̀.Láìpẹ́, Jacob dá ilé iṣẹ́ ipò òògùn tirẹ̀ tí ó pè ní egbògi Alábùkún, níbi tí ó ti ń pọ oríṣiríṣi oògùn àtinúdá tirẹ̀..Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Terry McOlùlan (Ọjọ́ìbí October 18, 1951) je Olùkọ̀wé Ara Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasí ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Abayomi Gabriel olonisakin jẹ́ ọ̀gágun ní ilé-iṣẹ́ jagunjagun orí-ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Lọwọlọwọ Ọ̀gágun olonisakin ni ògá àwon ọmọṣẹ́ ologun ilẹ̀ Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari ló yàn sípò yìí ní ọjọ́ 13 oṣù keje 2015.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọ̀gá àwon Ọmọsẹ́ ológun Naiià Ọ̀gágun ará Nàìjíríààwọn Ọmọsẹ́ ológun ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oga awon ọmọṣẹ́ ologun Naijiria tabi Oga Ile-ise ologun Naijiria (Chief of defence staff, Cds ni ede Geesi) ni ọmọṣẹ́ ologun ti ipo re gajulo ni arin awon ile-ise ologun ati olori gbogbo awon ile-ise ologun.. | wikipedia | yo |
Ipò yìí jẹ́ fún ọ̀gá ológun tí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà yàn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dá ipò yìí sílẹ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ lábẹ́ òfin-ìbágbépọ̀ Nàìjíríà ọdún 1979.Ọ̀gá àwọn Ọmọsẹ́ ológun Nàìjíríà únjíṣẹ́ tààrà fún ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà Botíjẹ́jẹ́ ìmójútó àwọn ilé-iṣẹ́ ológun Nàìjíríà wà lábẹ́ alákóso ètò àbò.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ́ àti láàkani ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ ológun Nàìjíríà ni láti da àti ṣe àwọn iṣẹ́ àti ètò fún abo orílẹ̀-èdè àti láti ríi pé àwọn ilé-iṣẹ́ ológun wà ní ìmúrasílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Egungun tàbí ẹ̀gún tàbí eegun ní ìfun inú ara líle tó ṣe àpapọ̀ gbogbo egungun-ara àwọn ẹranko elégungun.. | wikipedia | yo |
Awọn Egun únṣe abo fun oriṣi awon ìfun inu ara, won unṣẹ̀dá awon ihamọ ẹjẹ pupa ati ihamọ ẹjẹ funfun ti wọn jẹ akoonu ẹjẹ, wọn únṣe ìkọ́pamọ́ awọn ohun ewulókun, wọn únṣe ọna-iko ati imuduro fun ara, wọn si ungba imurin ni aye.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀gún gún wà ní oríṣiríṣi ìrísí, òṣì ní oríṣiríṣi ìrísí nínú àti lóde.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe bẹ ní fúyẹ́ síbẹ̀ wọ́n le gan wọn sí wa fún oríṣiríṣi iṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Egungun rato (osseous tissue), tí atunle pè ní Egungun ninu Àìlèka ninu ọ̀rọ̀ yẹn, òjé Tishóo tó le, òjé nkan gbógì tọn sọ Tishóo papọ̀, ọ̀fẹ́ fara pe afárá oyin ninu, tí ó ṣe ìrànlọ́wọ́ fún dídúró ṣinṣin.. | wikipedia | yo |
Tish egungun, oríṣiríṣi ẹ̀yin egungun lókórajọ pọ̀ láàfin pé ní Tishoo egungun.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn jẹ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìlera (Health Science) tí ó rọ̀ mọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìṣègùn (Medical Science), pẹ̀lú ìmọ̀ nípa ipò kẹ́míkà (Chemistry) mọ́ra wọn.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀kọ́ yi da lori iṣhan ipese, iṣakoso,didanu, lilo ati bi oogun naa yoo ṣe bára mu.. | wikipedia | yo |
Fífi iṣẹ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn ṣíṣe gbà í ènìyàn ò nímọ̀ tó lọ́ọ̀rìn nínú ìṣègùn, bí àwọn èròjà inú oògùn ṣe ń ṣiṣẹ́, ìpalára tí ó lè mú wá, ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú àìsàn tí a fẹ́ lòó fún, lílọ bíbọ̀ rẹ̀ nínú eéje, àgọ́ ara àti ìjàmbá tí Ọ̀gw náà lè fà bí kò bá tó tàbí pọ̀jù.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, Eko yí tún nílò kí eniyan mọ nipa (Pathology).. | wikipedia | yo |
Ibi tí a ti ń tà tabi ra òògùn ni a mọ̀ sí ilé òògùn (Pharmacy) tabi (Chemist).. | wikipedia | yo |
Kódà, iwọ̀nu ma ń wáyè laarin ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn àti àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì tó kù lọ́pọ̀ ìgbà láti lè gbé àwọn àṣàyàn oògùn kọ̀ọ̀kan jáde.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀ka ìmọ̀ Ọlọrundòsókè ni a ma ń kà sí IPsìsórí kẹrin emninu ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn.. | wikipedia | yo |
Lóòtọ́, ìmọ̀ Ọlọrunsókè ṣe pàtàkì ninu ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn (Pharmacy), àmọ́ òun kọ́ ni ó gbé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn ró.. | wikipedia | yo |
Ìlànà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nípa Pharmacy àti Ọlọ́runkìló yóò gbà kẹ́kọ̀ọ́ lórí àwọn iṣẹ́ wọ̀nyí yóò sì yàtọ̀ síra wọn.. | wikipedia | yo |
PharmacoInforjah naa tun jẹ ọkan pataki ninu ẹka imọ ìpoògùn ti o nísẹ́ pẹlu iṣṣàwárí ilana ti a le fi gbé oògùn kalẹ̀, gbe jade ti yoo si sise ti a fe ati bi a se le se itọju oogun naa ki o ma ba bajẹ.. | wikipedia | yo |
Pharmacogenomics tún dá lé Àru nípa ìbáse àwọn lẹgbẹ-ń-jáde inú omi, ìṣàn àti ẹ̀jẹ̀ ara àti ììṣesí àwọn là-ń-jáde yí sí àwọn oògùn tí wọ́n pèsè lẹ́yìn tí wọ́n lọ́dì nínú nínú àgọ́ ara.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Isẹ́ Ọpẹ́-kíkọ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn iṣẹ́ ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Nínú iṣẹ́ yìí bákan náà ni a ti máa ń gbà ògùrọ̀ tàbí ẹmu... | wikipedia | yo |
O ma ń ṣe ìpinu lórí ohun-kohun tó ṣẹlẹ̀ sí ènìyàn, ti yóò sì jẹ́ kí gbogbo ara ó mọ ohun tí o ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Inú egungun agbárí ènìyàn ni ọ̀pọ̀lọ́ wà ní orí ènìyàn.28 ni ó jẹ́ ìpín ọpọlọ tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìpín ọpọlọ ọmọnìyàn.. | wikipedia | yo |
CoTex yí ni ó tún pín sí NeoCorTex àti funracorTex tí ó sì kéré jùlọèyíkéyí nínú àwọn ìpín ọpọlọ yí ni wọ́n so pọ̀ pẹ̀lú Commissural nerve Tracts, tí ó jẹ́ Corpus callóṣùm.Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa ọpọlọẸ̀ka Ẹ̀kọ́ tí ó níṣe pẹ̀lú Ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ọpọlọ ni wọ́n ń pè ní NeAnatomyAnatomy, nígbà tí ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa bí ọpọlọ ṣe ń ṣiṣẹ́ ni wọ́n ń pè ní Neẹ̀sìnScience.. | wikipedia | yo |
Orisirisi ilana ni won n gba kẹkọọ atibse iwadi nipa ọpọlọ, lara re ni Aṣojútyl lati ara awon eranko ni Represenined Microtersárakúpa.Awon itọkasianti.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ ilẹ̀ Angola ránka ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ní orílẹ̀-èdè Angola.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ tí wọ́n gbàtọ́ ní ọdún 2010 ṣe sọ, ipò Alátọ́ àgbà jẹ́ píparẹ́; agbára aláṣẹ bọ́ sí ọwọ́ Ààrẹ.. | wikipedia | yo |
Ìgbà ẹ̀méjì fún ọdún márùún ni Ààrẹ lè fi wà ní ipò.Ní oṣù kínní ọdún 2010 ní Iléìgbìmọ̀ aṣòfin fọwọ́sí òfin-ìbágbépọ̀ tuntun, lábẹ́ òfin yìí, olórí ẹgbẹ́ òṣèlú tó ní iye ìjókòó tó pọ̀ jùlọ ní iléaṣòfin ni yíò di Ààrẹ, kò ní jẹ́ dídìbòyán tààrà látọwọ́ àwọn aráàlú. Lourenço ní Ààrẹ ilẹ̀ Angola lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí orí ipò ní 26 September 2017.Àtòjọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ Angola (1975-d'òní)ẹ tún woAngola ààrẹ ilẹ̀ Angoláàlàkókokóko àgbà ilẹ̀ Angolaa àwọn alákọ́so àgbà ilẹ̀ Angolanwọ́n ìtọ́kasí ilẹ̀ Angola Angola.. | wikipedia | yo |
Orílẹ̀-èdè Olómìnira onímàle ni ilé aládàáni kan tí ó unlo àwọn òfin onímàle fún ìjọba, ó sì yàtọ̀ sí Ilẹ̀ọba onímàle.. | wikipedia | yo |
Fún lílò ní orúkọ, àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́rin ló jẹ́ orílẹ̀-èdè Olómìnira onímàle.. | wikipedia | yo |
Àwọn wọ̀nyí ní Afghanistan, ìran, Mauritania and Pakistan.. | wikipedia | yo |
Pakistan ló kọ́kọ́ lo orúkọ yìí ní 1956 Lábẹ́ Òfin-ìbágbépọ̀; Mauritania bẹ̀rẹ̀ sí ni loo ní 28 November 1958; ìran bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó lẹ́yìn ìjídìde àwọn ará ìránní 1979 tó gbàjọba lọ́wọ́ PaHLA lárau; àti Afghanistan bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó ní 2004 lẹ́yìn ìwólulẹ̀ ìjọba Talibáni.Àtòjọ àwọn ORÍLẸ̀-èdè Olómìnira onímàleìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Olómìnira onímàle ilẹ̀ Afghanistan ní olórí orílẹ̀-èdè àti Olórí Ìjọba ilẹ̀ Afghanistan.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní AshRAF Ṣebídes.Ki wọn ó tó ṣe ìdásílẹ̀ ipò Ààrẹ orílẹ̀-èdè olominira onímàle ilẹ̀ Afghanistan ní 2004, Afghanistan tilẹ̀ ti jẹ́ orílẹ̀-èdè Olómìnira onímàle láti arin ọdún 1973 àti 1992 àti láti ọdún 2001 síwájú.. | wikipedia | yo |
Ní arin ọdún 1992 àti 2001, nígbà ogun abẹ́lé, Afghanistan jẹ́ mímọ̀ bíi orílẹ̀-èdè onímàle ilẹ̀ Afghanistan, àti lẹ́yìn náà bíi ìlórátì onímàle ilẹ̀ Afghanistan.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Edvin "Edièdì Rama (ojoibi 4 July 1964) ni oloselu, Agban-Àwòrán, Olukọwe, Apolongo, olukọ tẹlẹ, ati agbabọọlu-alápẹ̀rẹ̀ ará Albania, ohun ni ẹni 33k lọwọlọwọ to wà ní ipo alakoso agba ile Albania (lati 13 September 2013) ati alakoso ọrọ okere (lati 21 January 2019).. | wikipedia | yo |
Rama ló tún jẹ́ alága ẹgbẹ́ Sosiatóbẹ̃ ilẹ̀ Albania láti 2005.Kò tó di Alakoso agba, Rama ti wà ní àwọn ipo míràn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan sí ipò alakoso ètò aṣa, odo ati ere-idaraya ni ọdun 1998, ipo to wa titi di odun 2000.leyin naa won dibo yan bii olori ilu kòna ni 2000, won si tun tunyan ni 2003 ati 2007.. | wikipedia | yo |
In 2013, the Coco of center-left parties led by edi Rama won the 2013 Parpersonantary election, defeating the center-right Éjíbítìco of Democratic Party of Albania's INCum Prime minister, Sali Beìtẹ̀jádeun.. | wikipedia | yo |
he was elected as Prime minister for a second term in the 2017 election.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Albania.. | wikipedia | yo |
Igbe ènìyàn tàbí ìmí jẹ́ àwọn ohun oúnjẹ tí a jẹ tí ó da amọ̀ tí kò dá tán nínú ikùn tàbí agbẹ̀du ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Igbe ma n ni awon èròjà fojufoju ti wọ́n ń pè ní (bacteria), (bíbíBin) àti díè (epili) * nínú àwọn sẹ́ẹ̀lì tí wọ́n ti kù, lẹ́yìn tí yóò si jáde láti ẹnu iho-idi, tí a ó sì ma pèé ní igbe nígbà tí a bá yà sílẹ̀ tanijọra àwọn igbegbẹ́ ọmọ ma ń fara jọ imi tàbí igbe àwọn ẹranko mìíràn pẹ̀lú ìrísí wọn pẹ̀lú awọ, lílé tàbí rírò ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí wọ́n bá jẹ́ jẹ́.. | wikipedia | yo |
Igbe ọmọnìyàn ma ń sábà ní òhun bí ikùn tàbí kẹ̀lẹ̀bẹ̀ tàbí omi lára láti lè jẹ́ kí ó rọrùn bí bá fẹ́ jáde lẹ́nu ihò-ìdí.Wọ́n sábà m ń lo ìbẹ̀rẹ̀ púpọ̀ jùlọ nínú àwọn àkọsílẹ̀ oríṣiríṣi.imí àti ìtọ̀ ma ń sábà ń ní àkọ́-rin-rin lásìkò tí a bá fẹ́ ṣe ga, àwọn méjẽjì yí ni wọ́n jẹ́ ẹ̀gbin ọmọnìyàn tó lágbára jùlọ.Àwọn ìtọ́kasí ẹ̀gbin ara ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Ohùn ènìyàn ni ó jẹ́ ìró kan tí ọmọnìyàn ma ń gbé jáde láti inú tán àna ọ̀nà ọ̀fun, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tàbí orin, ẹ̀rín, ẹkún ariwo àti ìbòsí (sseleing), àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ohun eniyan jẹ́ ohun tí ó jẹ́Badamọ́ ọmọnìyàn, tí ó níṣẹ́ pẹlu ìfunpọ̀ ati fífẹ̀ kẹ́lẹ́ ọ̀fun eniyan nígbà tí wọ́n bá fẹ́ gbé irọ́ kan tabi òmíràn jáde.. | wikipedia | yo |
Lara awon irufe iro miiran ti ohun tun le gbe jade ni ifẹ ati isọ-wúyẹ́.awọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Tẹlifóònù ni ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀-jíjìnnà kan tó ungba àwọn olùṣeùn méjì tàbí púpọ̀ ní àyè láti sọ̀rọ̀ sí ara wọn tààrà nígbà tí wọ́n bá jìnnà sí ara wọn.. | wikipedia | yo |
TẸLIFÓÒNÙ Unṣiṣẹ́ nípa yíyí ohùn, àgàgà ohùn ènìyàn, sí àwọn àmì ìṣiṣẹ́ ẹ̀rọ-oníná tí wọ́n ṣe é gbé pẹ̀lú wáyà, àti àwọn ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ míràn, lọ sí orí tẹlifóònù míràn tí yíò ṣe atúngbéjáde ohun náà fún ẹni tó únọgbòò níbòmíràn.. | wikipedia | yo |
Ìtumọ̀ tẹlifóònù jáde láti (Teli, oókan) àti phone (fóònù, ohun), lápapọ̀ tí wọ́n túmọ̀ sí ohun oókan (Distant Voice).. | wikipedia | yo |
A tún lè pèé lásán ní fóònù.Ní ọdún 1876, Alexander Graham Bell ló kọ́kọ́ gba ìwé àṣẹ ìdola ní Amẹ́ríkà fún èrò kan tó gbé ohun ènìyàn jáde kedere.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀rọ yìí gba àtúnṣe lọ́wọ́ àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn míràn, nítorí bẹ́ẹ̀ ó di ohun ìlò dandan fún ìkówọ́, ìjọba, àti àwọn agbolé.Ẹ̀rọ tẹlifóònù ní gbohùngbohùn kan (ẹ̀rọ Ìfiránṣẹ́''', fẹ́té) láti fi sọ̀rọ̀ àti èrò ìgbọ́ran (èrò Olùgbà, Ṣódver) láti fi gbé ohùn jáde.. | wikipedia | yo |
Bákannáà, tẹlifóònù tún ní àgọ́’’ tó ún polongo ìpè tẹlifóònù tó únbọ̀, ó tún ní èrò Ayíwo tàbí bọ́tìnì láti fi tẹ nọ́mbà tẹlifóònù fún ìpè tẹlifóònù míràn.. | wikipedia | yo |