cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nínú wàrà ní KolositiRóòmù tí ó jẹ́ èròjà àsá-lóore gan an sódò sí nígbà tí èyíkéyí ẹranko àlègún lẹ́yìn àfòmọ́ lọ́mú bá kọ́kọ́ fọmọ rẹ̀ lọ́mú..
wikipedia
yo
KotiraRóòmù yi ni o kun fun èròjà ọmọ ogun ara tí ó ń jáde lati ara ìyá sí ara ọmọ rẹ̀ tó ń múye lati dáàbò bòó kúrò lọ́wọ́ àrùn àti àìsàn fojufoju, ó tún kún fún àwọn èròjà mìíràn tó ń ṣara-lóore..
wikipedia
yo
Mokg ER ke Kabewe Gakoko (ojoibi 21 July 1961) ni Aare ile Botswana ikarun lọwọlọwọ, lati ọdun 2018..
wikipedia
yo
O jẹ alakoso eto Eko tele ati alakoso ọrọ ise Aare ati imojuto igboro lati 2011 di 2014..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ dìbò yàán sí ilé-aṣòfin ní 2009.Ìtọ́kasíàwọn ara Botswanàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Botswana..
wikipedia
yo
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Botswana ni olórí orílẹ̀-èdè àti Olórí Ìjọba ilẹ̀ Botswana, bakanaa ó tún jẹ́ aláṣẹ àgbà ilé-iṣẹ́ ológun, nílànà bí òfin-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ Botswana ṣe sọ.Politicalkey Parties:Symbols Died in officeàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Botswana (1966-doni)ìgbà àsìkò ayé àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Botswanhis is a graphical Lifepanpan Timeline of presidents of Botswana..
wikipedia
yo
Felix Antoine tshisekédì Shíilo (; Ọjọ́ìbí 13 June 1963) ni oloselu ara nko to ti je Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóńgò lati 25 January 2019.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ara Orílẹ̀-èdè Olómìnira toṣèlúayé ilẹ̀ Kóńgò..
wikipedia
yo
Betty Shabacasal (orukọ àbísọ Betty Dean Sanders; May 28, 1934 – June 23, 1997), ti a tun mọ bákannáà bii Betty X, jẹ́ olùkọ́ àti alákitiyan àwọn ètò aráàlú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
ShabaMáun ni iyawo Malcolm X.Àwọn ìtọ́kasíàwọn alákitiyan ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Iwe, jẹ ẹya ara kan ti iṣe rẹ da lori lilo ounjẹ ti a jẹ ninu ti o ti da ninu pupọ ẹranko..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà ara yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ara.Ìrísí rẹ̀iwe rí róbótó, tinú tẹ̀yìn rẹ̀ jẹ́ kìkì iṣan tí ó sì ma ń lo oúnjẹ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn òkúta wẹ́wẹ́wẹ̀.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Apata jẹ́ ohun rìbìtì tí ó ń ṣẹlẹ̀ fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ohun àlùmọ́nì..
wikipedia
yo
Apata jẹ́ ohun tí ó fojú hàn jùlọ ní orí-ilẹ̀.Ẹ̀ka ìmọ̀ tí a ti ń kọ́ nípa àpáta, ìrusókè àti àtòjọ rẹ̀ ni wọ́n ń pè ní Petrology ni èyí tí ó sì jẹ́ abala kan lára ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa ilẹ̀ (géology).Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìrì, ẹ̀rí, dáwọ́ tàbí níní jẹ́ omi kan tí ó má ń sẹ̀ tàbí kóra jọ sí orí ewé, koríko tàbí ohun kan mìíràn tí ó bá wà ní abẹ́ sánmọ̀ ní òru mọ́jú tàbí lásìkò tí ojú ọjọ́ bá bora..
wikipedia
yo
Ohun tí ìmọ̀ fún múlẹ̀ ni wípé nígbà tí òru tàbí ìgbóná ojú ọjọ́ bá ń bora tí afẹ́fẹ́ tútù ń fẹ́, òru ara àwọn ewéko àti àwọn ohun mìíràn tó ti gbóná jàn Jan lójú ọjọ́ tẹ́lẹ̀ yóò ma ṣe òru èyí tí kò láyé láti gbéra gòkè lọ tí wọ́n ń pè ní (E-àpòv), ìjákulẹ̀ yí ni ó ma ń fàá tí irúfẹ́ òru bẹ́ẹ̀ fi ma ń sílẹ̀ sí orí àwọn ewéko gbogbo.Gileadi></Ref.làwọn àsìkò kan tí oòrùn kò bá mú da bí nkan láwọn agbègbè oókan, èyí lè mú kí ìrí ó di pọ̀ kó di yìnyín, ni èyí tí wọ́n ń pe ìkórajọ pọ̀ yí ni (Frost) tí ó jẹ́ wípé ìrì niṣẹ́ pẹ̀lú bí ojú-ọjọ́ bá ṣe rí tàbí gbóná sí, ó sábà ma ń ṣe sí ara àwọn nkan bíi ewé, koríko, ojú irin ọkọ̀ ojú-irin, orí tàbí ara ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí..Àwọn
wikipedia
yo
Ewé jẹ́ àkójọ pọ̀ orúkọ fún àwọn etuntun igi ọkàrisi tí a lè fojú rí.Ìrísí rèéwe jẹ́ ohun ti o ma ń sábà rí pẹlẹbẹ, o ma ń ni ilá tẹ́ẹ́rẹ́ láàrin bí ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí ni ewé rẹ ṣe ma ń fàlà sára..
wikipedia
yo
Ewé sábà m ń hù sí ara tàbí orí igi lọ́pọ̀ ìgbà, èyí náà tún dá lé irúfẹ́ ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Ewé ma ń dàgbà sókè látàrí omi àti ìtànṣán oòrùn (photosynthesis) tí ó bá tàn sí ni ó fi ń gbéra sókè..
wikipedia
yo
lọ́pọ̀ ìgbà, gbogbo ewé kọ́ ló ma ń rí bákan náà, ọ̀pọ̀ ma ń dán lára,ọ̀pọ̀ sì ma ń laìní,ọ̀pọ̀ ma n ni e[[Ẹ̀gún lára, nígbà tí ọ̀pọ̀ má hánì lọ́wọ́ ..
wikipedia
yo
ohun tí ó ma ń sọkún fa àwo olómi aró gírìni tí ewé ma n ni ohun tí wọ́n pè ní Kílọ́fífi (chlorophyll)..
wikipedia
yo
èròjà yí ṣe.pàtàkì fún irú lọ́gọ̀ àti ìṣẹ̀dá ewé ati igi lọ́pọ̀, nítorí oun ni ó yírá padà sí ounjé fún ewé ẹ̀yìn tí ó bá ti gba itan ọrun òso ṣlẹ̀.Awon ìtọ́kasíàwọn ọ̀gbìn..
wikipedia
yo
Nínú ètò ìlera àwùjọ, (paradà-síra-ẹni lójúkojú), jẹ́ ìlànà tí kìí ṣe nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìlò oògùn pẹ̀lú èròńgbà láti dènà títanka àjàkálẹ̀ ààrùn nípa jíjìnnà sí ara ẹni lójúkojú láti ṣe àdínkù iye ìgbà tí àwọn ènìyàn lè súnmọ́ ara wọn pẹ́kípẹ́kí..
wikipedia
yo
O jẹ mo isediwon bi eniyan kan se le jinna si ẹlomiran (iru òdiwọn bẹẹ maa n yàtọ lati igba de igba ati ni orilẹ ede kọọkan) ati ajinde fun ipekọ opo èèyàn.Nípa Ed-síra-ẹni, o se e se ki àdínkù wa fun kiko ajakale ààrùn ran eni ti ko Lápo eyi ti o le waye nipa didara pộ mộ ẹni ti o ti ko aarun, ti eyi yoo sin şe àdínkù iye ẹni ti aarun bẹẹ le pa..
wikipedia
yo
A máa ń lo ìlànà yìí pẹ̀lú ìwà ìmọ́tótó èémí àti fífọwọ́ ẹni..
wikipedia
yo
Nigba rògbòdìyàn ajakale aarun erankorona 2019, ajo eto ilera agbaye, World Health Organization (WHO) dabaa lati ṣẹ̀gbé fun Ebàá-sira-eni ti o tako Eal-sáwùjọ-eni, lati ṣalaye pe E-sira-eni ni o le ṣe àdínkù kikọ ajakalẹ aarun naa, awon eniyan si le ni ibaṣepọ to dara nipa lilo imọ-ẹrọ..
wikipedia
yo
Láti ṣe àdínkù ìgbràn ajakalẹ aàrùn àti láti dènà iṣẹ́ àṣekúdórógbó fún àwọn elétò ìlera, pàápàá jù lọ nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òfin ẹkún-òdì ni wọ́n là kalẹ́, lára wọn ní títì ilé-ìwé àti àwọn ilé ijọsin pa, ìdágbé, ìsẹ́ra-ẹni dènà àjàkálẹ̀ ààrùn, òfin kónílégbélé àti gbígbẹ́gi ìpéjọpọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé séẹ́ńtúrì kọkànlélógún yìí ni ọ̀rọ̀ náà jẹyọ, lílo ẹkún-síra-ẹni láwùjọ ti wá láti láti nǹkan séẹ́ńtúrì mẹ́ẹ̀ẹ́dógún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ náà jẹyọ nínú Bíbélì, nínú ìwé Léfítíkù, orí kẹtàlá, ẹsẹ kẹrìndínláàádọ́ta, “Adẹ́tẹ̀ náà tí ó ń ṣàìsàn ní ....
wikipedia
yo
Yóò máa nìkan dá gbé lẹ́yìn níbi ọ̀tọ̀, ibi ọ̀tọ̀ yìí ni yóò sin máa gbé.” Nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn àwọn ará Jositigbè lọ́dún Lọ́dún sí 542, Olórí àwọn Jositigbé àkókò ṣòfin IyaIbùdó Dènà àjàkálẹ̀ ààrùn ni abẹ́ àṣẹ ìjọba Byzantine, lára àwọn òfin ìyáèrè dènà àjàkálẹ̀ ààrùn náà ni Jùjú Òkú sínú Òkun, ó sọ ní àìmọye ìgbà pé àwọn ará Júù, Samáríà, àwọn abọ̀rìṣà, àwọn elékèé, ìwà abo abo máa bá abo sùn sùn tàbí kí akọ máa bá akọ sùn pẹ̀lú àwọn ìwà ẹ̀ṣẹ̀ mìíràn ló fa àjàkálẹ̀ ààrùn nígbà náà”
wikipedia
yo
Láyé òde òní, lílo ẹkún-síra-ẹni dènà àjàkálẹ̀ ààrùn wáyé láti dènà onírúurú àjàkálẹ̀ ààrùn..
wikipedia
yo
Nígbà St. Louis, ní kéè lẹ́yìn ibèsílẹ̀ ìajakalẹ̀ ààrùn, Influenza ṣẹ́yọ láàárín ìlú dún 1918, àwọn aláṣẹ pàè títí àwọn ilé-ìwé pa, gigi dínà kọ̀pọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn àti aayan E-ìyà-ìyà mìíràn..
wikipedia
yo
Iye awon eniyan to ku ni St. Louis nigba naa ko po to ti Philadelphia, ti won ko ṣàmúlò ẹkún-síra-ẹni nigba ibesile ajakale aarun Influenza, afi leyin ose meji ti ajakale aarun naa bẹ sile..
wikipedia
yo
bẹ́ẹ̀ náà, àwọn aláṣẹ ti dámọ̀ràn ẹkún-síra-ẹni nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn erankorona 2019..
wikipedia
yo
Awon ilana idena ajakale aarun wonyi le maa sise to ti iru ajakale aarun naa ba je eyi ti eniyan le ko nipa jijẹ ounje tabi omi ti aarun ti kóbá, tabi nipa eranko agbarunrin bii Efon, tabi awon kokoro miiran.Lára awon ìṣòro Eal-sira-eni ni wọnyi, ìdánìkangbe, idi ku iṣẹ ati sise awon nnkan elo ati pipadanu awon anfaani to jẹmọ́ ìbáṣepọ̀ láwùjọ eni.Awon anfaani re awon eniyan le yi pada nigba ti won ba mo pe ajakale aarun kan n ran kaakiri awujo nipa funfun fun ara eni ati awon ibi ìpéjọ láwùjọ..
wikipedia
yo
Bí a bá ṣe àmúlò èyí láti dènà àjàkálẹ̀ ààrùn, irú ẹkún-síra-ẹni láwùjọ bẹ́ẹ̀ lè ní ànfàní púpọ̀, ṣùgbọ́n yóò ṣe àkóbá fún ètò ọrọ̀-ajé..
wikipedia
yo
Ìwádìí fihàn pé, ṣíṣe èyí lóòrèkóòrè àti lẹ́sẹ̀kẹ́kẹ́ nìkan ló lè mú èsì tó dára jáde..
wikipedia
yo
ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmúlò ni wọ́n ń múlò láti dènà ríran ká àjàkálẹ̀ ààrùn..
wikipedia
yo
Eal-síra-ẹni láwùjọ.yíyàgò fun ìfarakinra jíjìnnà si ara-ẹni ni iwọn bata mefa (ni u.S tabi U.K) tabi mita 1.5 (ni Australia) tabi iwọn mita kan (ní Faranse tabi Italy) si ara ati yíyàgò fún idimọra ẹni ati Àtòjọ àwọn iṣẹ́ mìíràn tí ó jẹ mọ́ ifarakanra máa n ṣe àdínkù kikọ aarun nigba ajakalẹ aarun flu ati erankorona lodun 2020..
wikipedia
yo
Ṣíṣe imulo àwọn ìlànà ẹkún-síra-ẹni láwùjọ wọnyi, pẹ̀lú gbígbé ìgbé ayé ìmọ́tótó ni ibi iṣẹ́ wà lára ìlànà tó dára.Níbi tí ó bá ti ṣe é ṣe, wọn lè dá a lábàá pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ lati ilé.ọpọlọpọ ìlànà èyíwùmí ni wọ́n ti làálé fún àṣà ìbora-ẹni lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ìkíní nípa fífi ọwọ́ ẹni méjèèjì papọ̀ láìbo ẹni tí a ń kí lọ́wọ́, kíkíní nípa ìfọwọ́sọ̀yà, jẹ́ lára àwọn ọ̀nà ìkìra ẹni láìfara kanra..
wikipedia
yo
Ní àkókò erankorona 2019 lórílẹ̀-èdè United Kingdom]], iṣẹ́ ìkíni yìí ní ọmọba Charles lọ láti kí àwọn àlejò, ìkíni yìí ní Ọ̀gá-àgbà Àjọ ètò Ìlera Àgbáyé, WHO, Tedros Adhanọ̀m GHébReyesus àti olórí ìjọba orílẹ̀ èdè Ísírẹ́lì, Benjamin Adévyáhù náà tún là kalẹ̀ fún lílò ..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀nà èyíwùmí mìíràn ni; nína ọba-ìka sókè, jujuwọ́ sì ni, fi fọwọ́ ṣaya, bí wọ́n ṣe ń ki ara ẹni ni ní àwọn apá kan lórílẹ̀ èdè Iran.Ilé Ìkẹ́kọ̀ọ́ títí pàáwomo ìmọ̀ ìṣirò ti fihàn pé, Títí ilẹ̀ ìwé pa lè ṣe àsè ìdádúró..
wikipedia
yo
Bi o tilẹ wu ki o ri, iyọrisi rere rẹ da lori bi awọn akekoo mu ofin ẹkún-sira-ẹni láwùjọ nigba ti wọn ko si ni ile Eko..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn òbí mìíràn lè gba ìyọ̀ǹda ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́, bákan náà, wọ́n máa nílò láti ti ilé-ìwé pa fún ìgbà pípẹ́..
wikipedia
yo
Àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí lè fa ìfàsẹ́yìn fún àwùjọ àti ètò ọrọ̀-ajé.Ilé iṣẹ́ títí pàábajáde ìwádìí àwòkọ́ṣe àti ìfarawé lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà fihàn pé ìdámẹ́wàá (10%) nínú àwọn ilé iṣẹ́ tí wọ́n ti kọ́ àjàkálẹ̀ ààrùn ni wọ́n máa ń tì pa, àpapọ̀ ìkọ́ràn àjàkálẹ̀ ààrùn jẹ́ ìdá mọ́kànlá lé ìpín mẹ́sàn-án (11.9%),tí àsìkò kíkọ́ àjàkálẹ̀ ààrùn púpọ̀ máa ń fà sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ní ìdàkejì ẹ̀wẹ̀, ti ìdá mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33%) nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó kó àjàkálẹ̀ ààrùn bá wà ní títì pa, àǹfààní kíkọ́ àjàkálẹ̀ ààrùn yóò dínkù ní ìwọ̀n ìdámẹ́rin pẹ̀lú ìpín péréte mẹ́sàn-án (4.9%), tí àsìkò gíga àti kó ààrùn yóò fà sẹ́yìn fún ọ̀sẹ̀ kan..
wikipedia
yo
Lara ile-iṣẹ titi pa ni titi pa "Awon okowo ti ko se pataki" ati awon ise awujo to se pataki (awon okowo ti ko se pataki" tumọ si awon ohun elo fi bee wulo ni kiakia láwùjọ ohun-elo pataki workplace closures, eyi yato si awon ohun elo to se pataki láwùjọ.Ṣíṣe idaduro awọn ìpéjọpọ̀ eniyan pupolara gigidínà awọn ipepjọpọ tabi ipade opo eniyan ni; ipepjọpọ fun eto ere-idaraya, ile sinima tabi agbo-orin..
wikipedia
yo
Ẹ̀rí pé ìpèpjọpọ̀ ènìyàn púpọ̀ máa ń ràn ríran ká àjàkálẹ̀ ààrùn lọ́wọ́ ní kíákíá kò ì tí ì parí..
wikipedia
yo
Àbájáde ìwádìí anectaltal dábàá pé àwọn ìpèpjọpọ̀ àwọn ènìyàn púpọ̀ kan lè ràn ríran ká àjàkálẹ̀ ààrùn lọ́wọ́, àti wípé èyí lè fa àjàkálẹ̀ ààrùn wá sí agbègbè ti irú ìpèpjọpọ̀ bẹ́ẹ̀ bá ti wáyé, tí ààrùn náà lè bẹ̀rẹ̀ sí ní tàn kálẹ̀ láàárín ìlú nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn..
wikipedia
yo
Ní àsìkò àjàkálẹ̀ ààrùn ẹran lọ́dún 1918, ó ṣeé ṣe kí ó jẹ́ wí pé itọ́ lọ́wọ́ọ́wọ́ àwọn ọmọ ológun Philadelphia àti Boston ló fa ríran ka àjàkálẹ̀ ààrùn nípa ìdarapọ̀ àwọn àwọn awakọ̀ ojú-omi tí wọ́n ti lùgbàdì ààrùn ẹran pẹ̀lú àwọn ẹ̀rọ èrò àwọn ènìyàn tí kìí ṣe ológun..
wikipedia
yo
Ṣíṣe dádúró ìyìpọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn, pẹ̀lú àwọn àwọn al-ìkan-ẹni láwùjọ mìíràn lè dènà ríran ka òdì ààrùn.GiDúró àwọn irinajo láẹ̀-òkan- àwọn ẹnubodè pa tàbí gbígbẹ́ Dina irin-ajo elélé lè maa ṣàde jímọ̀ òṣẹ pàmọ̀ ju òsẹ̀ méjì sí mẹ́ta lọ, àyàfi bí wọ́n bá ṣe ètò náà, tí ó múmú ní ìdá pàmọ̀ ní ìdáwe (99% ní ìdá (99– ìdá ọdún *gbádùn * pé * * * * * * * * * , pẹ̀lú àwọn èwà * * * * * * * ** * * * * ní ìdá ọdún * ọdún * * * * * * ní wọ́n yẹ ní ìdá ìlú ní wọ́n * * ní àwọn pẹ̀lú ìdá ẹ̀mọ̀ ní ó pẹ̀lú pẹ̀lú * sí ìdá ìlú rẹ̀ ni ìdá àwọn oní ní ìdá ẹ- já pẹ̀lú ti àwọn oníbi àwọn tí ó tún fi ẹ kan * náà pé ẹni pẹ̀lú àwọn pẹ̀lú àwọn onílẹ̀ * sí ìdá àwọn oníkan tí wọ́n kan National náà * * * sí ìdá ẹ̀mọ̀ * * ****_
wikipedia
yo
Àyẹ̀wò fínnífínní ní pápákọ̀ òfurufú Canada kọ́ gbégi dínà àjàkálẹ̀ ààrùn SARS lọ́dún 2003 lórílẹ̀-èdè and the U.S.Àyẹ̀wò fínnífínní ẹnubodè láàárín Austria àti Ottoman Empire, tí wọ́n ṣe lọ́dún 1770 títí di ọdún 1871 láti dènà àwọn tí wọ́n ní ààrùn Bubobonic láti wọ orílẹ̀ èdè Australia, ni ìròyìn sọ pé ó ṣiṣẹ́, nítorí kò sí àjàkálẹ̀ ààrùn náà ní àwọn agbègbè Australia lẹ́yìn akitiyan náà, bẹ́ẹ̀ náà, àjàkálẹ̀ ààrùn jà rànyìnyìn ní agbègbè Ottoman títí di séẹ́ńtúrì ọ̀kàndínlógún.i wádìí ìjìnlẹ̀ kan ní Yunifásítì Owórin tí wọ́n tẹ̀ jáde jáde lóṣù kẹta Ọdún 2020 fihàn pé dídènà ìrìn-àjò láti orílẹ̀-èdè China sí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn àdínkù bá bi àjàkálẹ̀ ààrùn erankorona 2019 ṣe ràn káàkiri orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè, ṣùgbọ́n kò dènà ríran ká àjàkálẹ̀ ààrùn náà ní àwùjọ sí àwùjọ àti ènìyàn kan sí òmíràn..
wikipedia
yo
[...] nítorí ìdí èyí, dídènà ìrìn-àjò nìkan kò tó láti dènà àjàkálẹ̀ ààrùn, àyàfi bí wọ́n bá mú paradà-síra-ẹni láwùjọ mọ́ ọn." Ìwádìí náà fihàn pé, dídènà ìrìn-àjò ni ìlú Wuhan dènà rírán ka àjàkálẹ̀ ààrùn náà sí àwọn ìlú pàtàkì mìíràn ní China fún ọjọ́ mẹ́ta sí márùn-ún péré, lóòótọ́, ó dènà rẹ̀ fún orílẹ̀ èdè sí orílẹ̀-èdè ní ìwọ̀n 80%ìbora.ìbora-ẹni lára ìgbìyànjú ìbora ẹni ní ṣíṣe àdínkù ìfojúrinju kọ́rọkọ́rọ, ṣíṣe ètò káràkátà lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ tàbí lórí ìkànnì ayélujára, yíyẹra fún ibi ìpòkìkípọ̀ nlá àti gbígbàyanjú láti dẹ́kun ìrìn àjò afẹ́ tàbí ìrìn àjò tí kò pọn dandan. Àwọn alárùnlásìkò àjàkálẹ̀ ààrùn SARS lọ́dún 2003 ní orílẹ̀-èdè Singapore during the 2003 SARS outbreak in Singapore, ó tó ènìyàn tí wọ́n jẹ́ alárùn ni wọ́n yà sọ́tọ̀ tipátipá nílẹ̀ wọn, tí wọ́n sin mú kí n máa wòye ara wọn fún àmìn ààrùn, wọ́n sin ń pe àwọn elétò ìlera lókòló bí ọ̀nà láti dènà – dènà ààrùn..
wikipedia
yo
Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ènìyàn méjìdínlọ́gọ́ta péré ló ní ààrùn náà lẹ́yìn àyẹ̀wò, àwọn òṣìṣẹ́ ìlera gbà pé ọ̀nà náà kẹ́sẹjárí nípa ṣíṣe àdínkù títàn ká ààrùn náà..
wikipedia
yo
O le jẹ wi pe, yíyára ẹni sọ́tọ̀ láìnipa lọ láti ṣe àdínkù àjàkálẹ̀ ààrùn Influenza ní Texas lọ́dún 2009..
wikipedia
yo
Wọ́n ti jábọ́ bábá ṣdará ọ̀pọ̀ ìgbà díẹ̀ àti ìgbà Kpé.Oríkì E-ẹ̀kan KpéCenters for Disease Control and Prevention (CDC), èyí àni ìjọba tí ó ń rí sí òṣèlú ÀÌSÀN àti ìràpo ààrùn “ E- albi lábi gẹ́gẹ́ bí Alaalẹ́ lati ṣe idinku bí àwọn ènìyàn ṣe lè sunmo ara wọn ni gbogbo gbogbo igba ní gbogbo 2 2 yẹ 2". 2 2 Ogun flu dún tí Àjọ́ ti ó ń ṣe pẹ̀lú gbogbo ole ní agbaye, World Health, World Health, Who yìí-ẹ̀ gun lábi al- láwùjọ gẹ́gẹ́ "AÁYAN sí ẹni sí ẹni ní ìwọ̀n ní ìwọ̀n ní ìwọ̀n ní ṣiṣẹ́ ọdún ènìyàn ' ] gbogbo ọ̀fà tí ó yẹ ọdún al- já ní pẹ̀lú ẹ̀bi àwọn tí ó maa ṣe ní àwọn ẹni ( ìdá mọ́ ẹ tí ó ní gbogbo ọ̀gí ọdún ijó lati ọdún Nàìjíríà sí àwọn tí pẹ̀lú pẹ̀lú ìràkọ̀pọ̀ yìí ni gbogbo ìgbà tí ó ti ìpa elè we ẹ̀we ( gìn ní gbogbo tí gbogbo ọmọ ní ọdún National School ní àwọn ní ọdún *"Hailà ni wọ́n tún ń ṣiṣẹ́ sí ìdá gbogbo ń fi àwọn oníwo ní ọ̀gi ara Nàìjíríà ní gbogbo ìsin lati ẹni tí ó maa bí àwọn onípé sí àwọn oníkan ní ìdáni - ọmọ rẹ̀ ni ọdún tí ó ń rí ọdún * ẹ̀gi * àwọn bí bí pẹ̀lú pẹ̀lú ijò kan ní ẹni ní àwọn ènìyàn * pẹ̀lú àwọn tí*_
wikipedia
yo
Wọ́n pa á pọ̀ pẹ̀lú ìmí lọ́nà ìmọ́tótó àti ọwọ́ fífọ̀, èyí ni wọ́n kà sí ọ̀nà tó dára jù lọ láti ṣe àdínkù tàbí dènà àjàkálẹ̀ ààrùn láwùjọ.Nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn COVID-19, Àjọ CDC ṣe Àtúnṣe sí oríkì Ed-síra-ẹni láwùjọ, nípa ṣíṣe àfikún yíyẹra fún agbo ọ̀pọ̀ èèyàn àti jíjìnnà sí agbo ọ̀pọ̀ èèyàn, pàápàá jù lọ ní ìwọ̀n ) sí ẹnì kejì nígbà tó yẹ"
wikipedia
yo
Wọn kò ṣàlàyé ìdí kan pàtó tí wọ́n fi mú ìwọ̀n gúngùn ẹsẹ̀ mẹ́fà..
wikipedia
yo
Ìwádìí láìpẹ́ fihàn pé ìjàsílẹ̀ nígbà tí ènìyàn bá ń mí tagbáratagbára nígbà eré imárayá tàbí sìn lè rìn fún ìwọ̀n mítà mẹ́fà..
wikipedia
yo
Àwọn ẹlòmíràn ṣàlàyé pé òdiwọ̀n yìí wàyí láti ṣe akọdànù ìwádìí ìjìnlẹ̀ ọdún pípẹ́ ni 1930s àti 1940s tàbí ìpòrúru ọ̀kan lórí òdiwọ̀n náà..
wikipedia
yo
Awon olùwádìí ati awon onkowe sayensi ti se alaalẹ́ pe awon paradà-sira-eni nla ati lilo iboju tabi awon mejeeji pelu Eal-sira-eni láwùjọ se pataki.Awon itọkasiimo ajakale-arun imo nipa COVID-19 ti o se pataki..
wikipedia
yo
sánmọ̀ tàbí ojú ọ̀run jẹ́ gbogbo ohun tí ó wà lókè ilẹ̀ níbi tí òhun bí kurukuru, oòrùn, òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ ti ń yọjú wo ilẹ̀ lásìkò ìkọ̀ọ̀kan wọn.Ní inú ìmọ̀ ojú-ọ̀run, sánmọ̀ yí ni wọ́n ń pè ní Ahoho, níbi tí oòrùn, òṣùpá, àti àwọn ìràwọ̀ ti dàbí ẹni wípé wọ́n ń rọ kiriká ọ̀run fura rẹ̀,ní ọ̀gangan ilẹ̀.Ọ̀nà tí sánmọ̀ pín sísánmọ̀ tàbí ojú-ọ̀run yí náà pín sí ọ̀nà méjì..
wikipedia
yo
Àkókò ni kurukuru, èyí jẹ́ ipele àkókò àti ohun tí ó bo ojú-ọ̀run gan an fura rẹ̀.Èkejì ni Ahoho ọ̀run, ní í ti àwọn ìràwọ̀,oòrùn , àti òṣùpá tí ń yọjú lásìkò wọn gbogbo..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, kurukuru ojú sánmọ̀ ni ó súnmọ́ ilẹ̀ jùlọ tí ó jẹ́ wípé bí a bá gbójú sókè, òun ni àkókò máa rí.Àwọn àríwòye sànmọ́ni ojú mọmọ tàbí ní àsìkò ọ̀sán, ojú sánmọ̀ sábà má ń ní àwọ̀ búlúù tàbí yẹ́lò tí oòrùn yóò sì tàn kálẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìmọ́lẹ̀ tí a kò fi ní nílò iná tàbí ìhun kan mìíràn tí a lè fi òye rẹ̀ ríran ju òye ọjọ́ lọ.Bí ó ti di àṣálẹ́, sánmọ̀ yóò dúdú kẹ́lẹ́ kẹ́lẹ́, ni èyí tí ilẹ̀ náà yóò dúdú pẹ̀lú nítorí ìmọ́lẹ̀ sánmọ̀ ni ìmọ́lẹ̀ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ni àsikò yi, gbogbo ohun alàyè pátá ni wọn yóò nílò ohun tí ó lè jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọyẹ́ tàbí iná tí yóò ms fi wọ́n mọ̀nà..
wikipedia
yo
Àwọn àsìkò yí ni òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ yóò yọ tí wọn yóò sì tànmọ́lẹ̀ sí orí ilẹ̀..Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
ọmú tabi ọyàn jẹ ọkan pataki ninu ẹya ara tí o wà lọwọ òkè..
wikipedia
yo
Lára àwọn obìnrin, ó jẹ́ ẹ̀yà tí ó ma ń sun wàrà gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ fún àwọn ọmọ ọwọ́ tí wọ́n ń múmú..
wikipedia
yo
Àmọ́, ní àsìkò ìbàlágà ẹ̀yà ara yí ma ń dàgbà sókè lára abọ́ látàrí èròjà ara tí wọ́n ń pè ní (estrogen) àti (Growth hormone).Ọ̀rá tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ subcuTaneous fat tí ó níṣẹ́ pẹ̀lú ibùsùn omi tí ó ma ń jáde ẹnu kókó ọmú, àwo fẹ́lẹ́ yí ni ó ma ń fún ọmú ní àbùdá wọn..
wikipedia
yo
níparí ọmú ṣáájú kókó ọmú ní agbẹ̀du tí wọ́n ń pè ní Alveó ni omi ọmú ma ń sọ́dọ̀ sí tí ó sì ma ń wà ní sẹpẹ́ fún fífà tàbí mímu ìkòkò nígbà tí ọmọ bá gbẹ́nu sí..
wikipedia
yo
Lásìkò tí obìnrin bá wà nínú oyún, ọmú ma ń ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ èròjà àti ọmọ ogun ara tí wọ́n ń pè ní (Gáradó), pàá pàá jùlọ èròjà estrogens, ProÒrìṣàne, àti Prolactin, àti àwọn mìíràn bíi lólòbùdọ̀lar tí ó ń ṣiṣẹ́ fún ìdàgbàsókè àti ìgbaradì rẹ̀ fún ìfọ̀mọ́lọ́mú lẹ́yìn tí obìrin bá bímọ tán.Àríwísí nípa ọmú sí ṣíṣiṣẹ́ ìfmọ́ lọmú àti àwọn èròjà òdì-lóore tí ó kó sínú, wọ́n tún ka ọmú obìnrin sí àmì ìbàlágà obìnrin fún ìbálòpọ̀ láti ṣòwò ọmọ bíbí..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àti Orissa iṣẹ́ ọnà àti àwòrán ti ayé àtijọ́ àti tòde òní ni wọ́n ti ṣàfihàn ọmú ninu iṣẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ẹ̀yà orílẹ̀-èdè àgbáyé ni wọ́n ka ṣíṣáfihàn ọmú sí ìta gbangba gẹ́gẹ́ ohun ìríra tí kò sì bójú mu ní àwùjọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àdéhùn Igi Aláwọ̀-ewé ni Ìwé Àdéhùn Aláfojúwó Ìjà Ilẹ̀ tí ó kún fún Epo-ro í àti Afẹ́fẹ́ Gááṣì Ẹnubodè Láàárín orílẹ̀ èdè Cameroon àti Nàìjíríà tí wọ́n ń pè ní Bakassi..
wikipedia
yo
1981, Oija-akátá àwọn Ọmọ-òògùn láàárín Nàìjíríà àti Cameroon lọ́dún 1994, àti 1996 wáyé ní Bakassi.Wọ́n gbé aáwọ̀ ìjà yìí lọ sílé ẹjọ́ àgbáyé International Court of Justice, tí Ilé-ẹjọ́ sìn dá orílẹ̀-èdè Cameroon láre lọ́jọ́ Kẹwàá oṣù Kẹwàá ọdún 2002.Lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹfà ọdún 2006,Ààrẹ-àná orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ àti Ààrẹ orílẹ̀-èdè Cameroon, Paul Ribiya, tọwọ́ bọ ìwé-àdéhùn àdéhùn igi Aláwọ̀-ewé lórí kíkó àwọn ọmọ ológun kúrò àti fífi ètò ilẹ̀ náà sílẹ̀ fún orílẹ̀ èdè Cameroon..
wikipedia
yo
Nínú ìwé àdéhùn náà, wọ́n fún Nàìjíríà ní gbèdéke ọgọ́ta ọjọ́ láti kó àwọn ọmọ-ogun wọn kúrò, pẹ̀lú àfikún ọgbọ̀n ọjọ́ mìíràn, bákan náà, wọ́n fún Nàìjíríà ní àǹfààní láti sì ní àwọn olórí ìjọba àti ọlọ́pàá wọn ní Bakassí fún ọdún méjì mìíràn.Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ̀lé aṣe ìdájọ́ Ilé-ẹjọ́ Àgbáyé International Court of Justice, tí ó dá Cameroon láre kí wọ́n máa bá pàdánù ìrànlọ́wọ́ ilẹ̀-òkèèrè, wọ́ sin lọ àwọn ọmọ ogun wọn kúrò.
wikipedia
yo
Nígbà náà, wọ́n gbé ìgbìmọ̀ kan tó kún fún aṣojú Nàìjíríà, Cameroon, Àjọ Àgbáyé Un, Germany, Amẹ́ríkà, Faransé àti orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti ṣàbójútó títẹ̀lé ìwé Àdéhùn náàlọ́jọ́ kẹtàlá oṣù Kẹjọ ọdún 2013, Àjọ Kéréje Lábẹ́ Àjọ Àgbáyé, ún, tí ó ń rí sí ààbò United Nations Security Council ṣàlàyé pé òun fara mọ́ ìpètùs náà lọ́jọ́ méjì sí ọjọ́ ifálé ilẹ̀ Bakassissí.Àwọn Ìkaṣìpẹ̀Ace agreement..
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ sáyẹ́nsì nípa ilẹ̀, Ọ̀gbàrá jẹ́ wíwí omi àrọ̀dá ọjọ́ tí sẹ̀sẹ̀ rọ̀ tàn tí ó sì nn wọ́ yanrìn tàbí iyẹ̀pẹ̀ orí ilẹ̀ lọ bí òun náà ṣe ń wọ ruru láti ibìkan sí òmíràn..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, oko tí wọ́n fi ń ṣe nkan ọ̀gbìn tí ó wà ní Appalachian Mountains, ti di ojú odò ọ̀gbàrá látàrí àkọ́túnkọ́ ike ọkọ̀ náà ti mú kí wíwọ̀ ruru ọ̀gbàrá lágbègbè yí pẹ̀lú ẹrẹ̀ tí ó tó ọgọrun un (100x), tí ó sì ti mú kí ilẹ̀ oko náà jin kòtò gìrìwò.Àwọn ìpalára tí ọ̀gbàrá ń mú dání ruru ọ̀gbàrá er ọ̀jù lórí ike ti mú ìjàǹbá tó lágbára bá àwọn ilẹ̀, yálà ilẹ̀ ilẹ̀ tàbí ilẹ̀ oko..
wikipedia
yo
Àwọn ìpalára yí ni mímú àdínkù ba ohun ọ̀gbìn àti irè oko, jíjìn ilẹ̀ látọwọ́ ọ̀gbàrá nla, bíbà àwọn èròjà àti ọ̀rá inú ilẹ̀ jẹ náà kò gbẹ́yìn..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, ilé tí ọ̀gbàrá bá ti bàjẹ́ ma ń di ẹ̀kọsílẹ̀ nítorí ìbẹ̀rù omíyalé.dídá oko lójú kan ládàá ju (únKòb farming) àti ìgẹ̀ lulẹ̀ lábàadì (Detúmọ̀níbẹ̀), kíkọ ojú ọ̀nà àti àwọn ìṣesí ọmọnìyàn mìíràn tó lámì-laaka lórí ilẹ̀ náà ń ṣokùnfà bí ọ̀gbàrá ṣe ń ṣọṣẹ́ káàkiri àgbáyé..
wikipedia
yo
àmọ̀sá, Orissa Ọna ni àwọn eniyan n gba lagbaye lati mu àdínkù ba ose ọ̀gbàrá tabi lati dẹkun rẹ pata pata.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Fály ipupa n'Simba (ọjọ́ìbí December 14, 1977), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgé rẹ̀ fàlly ípupa, ni akọrin-akọ̀wé, oníjó, ọlọ́rẹ, onigita àti olóòtú ara Kóngò..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1999 dé 2006, ó jẹ́ ìkan nínú ẹgbẹ́ olórin Quarer Latin International, tí kòffi olómide dásílẹ̀ ní 1986.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn olórin ara orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò..
wikipedia
yo
Olusola Isola Ogunsola, ti opo eniyan mo si iṣho Pepper ni won bi ni ojo kerinla osu Kọkànlá odun 1942 si idile Ogbeni Samuẹli Ogunsola, ni agbolé Baala dáṣàolu leyin Mọ́ṣáláṣí Ita igbeyin ládùúgbò Òkè itoku ni ilu Abeokuta ni Ipinle Ogun.eto Eko reOlusola gege bi imgbẹ̀yìn ninu omo merin ti awon obi re bi, Abule olókúta, ni Eroko Alaho to wa ni ijoba ibile Oluyọ nilu Ibadan lo ti lo igba ewe rẹ, bakan naa lo lo si Ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Christ School, ti Ìlú olókúta.ise re gege bi osere Tiata iwe mefa, o pada si Abeokuta nibi ti o i bẹrẹ Ile-ẹkọ Abeokuta Grammar School, Ile-ẹkọ yi naa lo wa ti o ti n se ṣafihan Ife rẹ si ere tiaa..
wikipedia
yo
Lásìkò tí à ń wí yìí, ọ̀pọ̀ ènìyàn ló kórìíra iṣẹ́ yí nítorí wípé wọ́n ka àwọn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ yí sí alágbe lásán..
wikipedia
yo
Fundi eyi, Inirúurú ìpèníjà lo dijú ko Olusola nidi iṣẹ́ ti o yan laayo, débi wípé awọn ẹbí oun ọ̀rẹ́ ló kẹ̀yìn sí aya fi ìyá rẹ Abigail lọ̀ Ygbaa rẹ, tí o sì fọmọ pọn on kí o le sori ire..
wikipedia
yo
Olusola dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré ti gbajú-gbajà òṣèré Akin Ogunru dá sílẹ̀ ní ìlú Abeokuta ní ọdún 1959, lẹ́yìn tí ó parí ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó jẹ́ òṣèré tíátà ẹlẹ́kẹrin tó ya eré sinimá Àgbéléwà lẹ́yìn tí Hubert Ogundé, jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ ṣe bẹ́ẹ̀, èyí tó gbé lọ sí orílẹ̀-èdè United Kingdomipa rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ òṣèré tíátàOlúṣọlá jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn àgbà ọ̀jẹ́ òṣèré tíátà tó dá ẹgbẹ́ antp sílẹ̀ lọ́dún 1976..
wikipedia
yo
Muhoyálà tàbí Muhammad (, ; C. 570 ce – 8 June 632 CE) jẹ́ olórí ẹ̀sìn, àwùjọ, àti olóṣèlú Árábù àti olùdásílẹ̀ ẹ̀sìn ìmale.Àwọn ìtọ́kagbè àwọn Árábùàwọn òjíṣẹ́ ẹ̀sìn ìmale..
wikipedia
yo
Molade Alexander Okoya-Thomas FCna, MFR, OFR, Kss (8 June 1935 – 2 February 2015) je onisowo ati Olore ara Naijiria.Ìtọ́kasí onisowo ara Naijiria..
wikipedia
yo
John Keegan de Lanwàyí (October 31, 1984) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Odeda je ijoba ibile ati ileto kan ni Ipinle Ogun, ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ yí wa ni A5 Highway.Ìjọba ìbílẹ̀ yí ni ibùsọ̀ ti o 1,560 km tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 109,449 gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn tí ọdún 2006 ṣe fi lọọlé..
wikipedia
yo
Ijoba ibile yi sunmo ipinle Oyo pẹkípẹkí, ti o si pààlà pèlú ìpínlè Oyo ni ilu alogi..
wikipedia
yo
nọmba ifiranṣẹ (postal Code) ijoba ibile yi 110.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ìjọba ìbílẹ̀ jẹ́ ìpele ìjọba ẹlẹ́kẹ́ta àti irúfẹ́ ìjọba tí ó jẹ́ ti àwa-ara-wa lẹ̀sẹ̀ kuku tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan lábẹ́ ìlànà ìṣèlú àwa-ara-wa..
wikipedia
yo
Ijoba ibile ma n sise labe ofin ati alakale ofin orile-ede bi awon asofin (legist) ati awon Amofin (Judiciary) se gbe kale ni orile-ede kookan..
wikipedia
yo
Ninu ilana eto ijọba apapọ (Federal State), ijoba ibile lo saba ma n wa ni ipo kẹta ninu ètò ìṣèlú..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀ àgbékalẹ̀ ètò ìjọba ìbílẹ̀ yàtọ̀ síra wọn ní orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè ní àgbáyé.Àwọn ìpínsísọ̀rí ìjọbaìpínsísọ̀rí ìjọba lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ (Federal Government) lábẹ́ ìjọba àwa-ara-wa (DeMOCrcy), ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Eyi lo n ṣakoso ijọba mejeji isalẹ Ijọba Ipinle, eyi jẹ ijoba aarin to tun lagbara ju ijoba ibile lo ijoba ibile tabi Ijoba ese kuku ti o kangun si awon ara-ilu.Awon itọkasi..
wikipedia
yo