cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ó jẹ́ atọ́kùn ètò fún NTA tẹ́lẹ̀ kí ó tó di aláṣeṣe fún ìwé ìròyìn tí TODAY Woman.. | wikipedia | yo |
Òun ni atọ́kùn ètò seriously Speaking tí ó jáde ní ọdún 2014.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí sí ìlú Ìbàdàn ní Ìpínlẹ̀ Oyo ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kẹjọ ọdún 1963.. | wikipedia | yo |
Oun ni ọmọ karun-un ninu àwọn ọmọ mọkanla tí àwọn òbí rẹ̀ bí.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Etátan Preparatory School àti Idia College ní Ìlú Benin ní Ìpínlẹ̀ Ẹdó.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Obafemi Awolowo University níbi tí ó ti gboyè nínú ẹ̀kọ́ dírámà.Iṣẹ bàbá rẹ fẹ́ kí ó di àsọrọ ṣùgbọ́n ó nifẹ sí eré ṣíṣe láti ìgbà tí ó wà ní ọmọde.. | wikipedia | yo |
Ìgbà tí ó ń ṣe àjígùnbánirọ̀ ní ọdún 1983 ní National Television Authority, ni ó ti kọ́kọ́ ní ànfàní láti ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Sokoto.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó parí ètò Agùnbánirọ̀ rẹ̀ ní ọdún 1984, ó kúrò ní sòkòtò lọ sí ìpínlẹ̀ Ẹdó láti di olùkọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ ti Uibazua II Grammar School.. | wikipedia | yo |
Ni ọdún 1985, ó padà sí iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ilé iṣẹ́ Bendel Broadcasting Service tí wọ́n wà padà yí orúkọ wọn sí ẹ̀dọ̀ Broadcasting Service.. | wikipedia | yo |
Ó fẹ́ Ikechukwu onyẹnokwe ni ọdún 1988, ó sì ti bí ọmọ mẹ́fà fún... | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn Igbeyawo rẹ, o kuro ni Ilu Benin lọ si ipinlẹ Eko.. | wikipedia | yo |
O kọ iwe ìfiṣe sílẹ̀ fún ẹ̀dọ̀ Broadcasting Service, ó sì darapọ̀ mọ́ Nigerian Television Authority ní Èkó.O ti ṣe atọ́kùn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀tọ́ fún nta.. | wikipedia | yo |
O fi iṣẹ́ NTA sílẹ̀ lẹ́yìn ọdun mẹ́ẹ̀dógún tí o ti n sì ṣe fún wọn.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2000, o beere eto obinrin ode oni pẹlu Adesùsù lori NTA, o si ṣe eto naa fun ọdun mẹwa.Ni ọdun 2007, Adesù gbe iwe iroyin ti today's Women ti o soro nipa igbesi aye awọn obinrin.. | wikipedia | yo |
Òun ni atọ́kùn ètò Tw bùkún lóri African Magic.. | wikipedia | yo |
Ni osu keji odun 2015, o se ìfọ̀rọ̀wáninilẹ́nuro fun olori orile-ede Naijiria nigba naa, Goodluck Ebele Jonathan.. | wikipedia | yo |
O beere eto seriously Speaking lori Channels TV ni Oṣu Keje ọdun 2014.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹjọ ọdún 2016, ó gbé ètò vlog rẹ̀ kalẹ̀ tí ó pè ní Speaking my mind with Adesùsù.. | wikipedia | yo |
oun ni ó ṣe Anti ní eré Ultimate Love tí àwọn ilé iṣẹ́ Multichoice gbé kalẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí Television personalities from Ìbàdànàwọn ènìyàn alààyèNigerian Television Talk Show HosṢáwọn Ọjọ́ìbí ní 1963Nigerian Women JournaGender in NigeriaTelevision in Nidelemen in Nigeria.. | wikipedia | yo |
Olúrémi Oyo (bíi ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún1962, ó kú ní ọjọ́ kìíní oṣù Kẹwàá ọdún 2014) jẹ́ ògbóǹtarìgì oníròyìn àti adarí tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni oluranlowo pataki fun olori orile-ede Naijiria ni odun 2003, Olusegun Obasanjo lori awon oro ikede, oun si ni obinrin akoko ti o ma de ipo naa.Iṣẹ o lọ si ile eko giga ti University of Lagos nibi ti o ti gboye ninu ero ibaraẹnisọrọ ati iroyin.. | wikipedia | yo |
O gboye Masters ninu International Relations ni ile eko giga ti University of Kent ni orile ede United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Olúrémi bẹ̀ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníròyìn ní ọdún 1973 ní Nigerian Broadcasting Corporation ti o ti wa yi orúkọ pada ṣii Federal Radio Corporation of Nigeria (FRCN).. | wikipedia | yo |
O darapọ mọ NAN ni 1981 gẹ́gẹ́ bíi alátúnṣe Ìròyìn, o si kuro ni ọdun 1985.. | wikipedia | yo |
Ó ti sí ṣe fún Inter Press Service News Agency àti International News Agency.. | wikipedia | yo |
Abdullámì Abubakar fi ṣe ìkan láàrin àwọn tí ó ṣe òfin fún Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O di oluranlowo pataki agba fun Olusegun Obasanjo ni ọdun 2003 lo ri ọrọ ikede.. | wikipedia | yo |
Ó di adarí fún ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn ti Nàìjíríà ní Oṣù Keje ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
O ku ni orile ede United Kingdom ni ojo kìíní osu Kẹwàá odun 2014.. | wikipedia | yo |
O gba ẹbun lati National Council of Catholic Women Organisation of Nigeria Merit Award ati National Award of Officer of the Order of Niger, OON, ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Nigerian Guild of Editors (ńgé), Nigerian Institute of Management (nim), Nigerian Institute of Public Administrators ati Nigerian Guild of Editors.Awọn itọkasi awọn oniroyin ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Articles with HcardsNancy Illoh jẹ́ akọ̀ròyìn, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ olóòtú ètò “MoneyShow” lórí Africa Independent Television, ó sì tún jẹ́ Olùdámọ̀ràn Media àti Alákòóso owó ilẹ̀ Áfíríkà ní dáaàṣààṣà.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ alákòóso àgbà ti African Economic Congress.Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta ní Illoh, ó sì jẹ́ àkọ́bí nínú ọmọ mẹ́fà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí i ní Ìpínlẹ̀ Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ kí ó tó wá lọ Yunifásítì Nnamdi Azikiwe, Awka níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè BSc.. | wikipedia | yo |
Nínú ìmọ̀ Parasírulogy àti Enlogy.Iṣẹ́ rẹ̀ Nancy Illoh jẹ́ agbéròyìn sáfẹ́fẹ́, àti olóòtú ẹ̀tọ́ nípa ọ̀rọ̀ owó-ìṣúná àti ètò ọrọ̀-ajé tí wọ́n máa ń fi hàn ní Nàìjíríà àti ilẹ̀ AduIlẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tó ń gbé ètò "MoneyShow" kalẹ̀, tí wọ́n máa ń fi hàn lórí Airt, tí wọ́n sì máa ń ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn ọmọ Africa lórí ètò ọrọ̀-ajé àti owó-ìṣú.. | wikipedia | yo |
Oun ati ẹgbẹ rẹ ti ṣe ifọrọwanilẹnuwo fun Aare ana ti African Development Bank, tọ̀rúkọ rẹ̀ n jẹ Donald Karùka, ojogbon John Kuffor, to jẹ Aare Ilu Ghana tẹlẹ, Adams Oshiomhole ati Sanusi Lamido Sanusi, ati bẹẹ bẹẹ lọ.. | wikipedia | yo |
Obi Jideuwa, tí ó jẹ́ ọba ìlú Issele Azagba, ní apá Ariwa Aniocha ní Ìpínlẹ̀ Delta fi joye Adbe Né kwù AAnato.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn ALAlààyè.. | wikipedia | yo |
EUenia Abu (Bii ni ojo mọkandinlógún oṣu kẹwàá ọdun 1961) jẹ oniroyin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, Akowe ati akewi.. | wikipedia | yo |
Òun ni atọ́kùn ètò ìròyìn tẹ́lẹ̀ fún Nigerian Television Authority (NTA) .. | wikipedia | yo |
O ṣe atọ́kùn ẹ̀tọ́ lórí NTA fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bíi sí ìlú Zaria ní ọdún 1962.. | wikipedia | yo |
Ó béèrè sì ni kọ̀wé láti ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méje.. | wikipedia | yo |
O lo si ile eko Abu staff School ni Zaria ati Queen Amina College ni Kaduna fun Eko ibẹrẹ pepe.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Ahmadu Bello University ní Zaria, ó sì gboyè nínú ẹ̀kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1981.. | wikipedia | yo |
O gboye Masters rẹ ninu imo ibaraẹnisọrọ ni ile eko giga ti University of London ni odun 1992.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ohun, ó sì ti gba owó ìjíè láti òdò Chevening scholarship.. | wikipedia | yo |
O da ẹgbẹ ti awọn ọmọde lati ọmọ ọdun meje si meedogun ti ma kawe ni ọdun 2018.. | wikipedia | yo |
Iwe rẹ, In the blink of an Eye jẹ ki o gba ẹbun Akowe binrin to tayọ jùlọ ni ọdun 2008.Àwọn Ìtọ́kasí Awọn Eniyan Alààyè, JournaboNigerian Broadcasters, Women Journansi of Birth Missing (Living People).. | wikipedia | yo |
Aisha Fálóde jẹ́ oníròyìn fún èrè Ori pàápàá ni Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni olori fun ẹgbẹ agbabọọlu obinrin fun orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó wà láàrín àwọn òṣìṣẹ́ tí ó kọ́kọ́ bẹ́ẹ̀ rè ní ilé iṣẹ́ tẹ̀lẹ̀Fisinù ti African Independent Television.. | wikipedia | yo |
O ti si ṣe pẹlu Nigerian telecommunication Limited ati Graduate TAon operators scheme.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí radìíó, ó sì má sọ̀rọ̀ nípa eré orí pàápàá.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kìíní Ọdún 2017, wọ́n fi jẹ́ olórí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin fún orílẹ̀-ède Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè, Television Journansi of Birth Missing (Living People)Yorùbá Journalle Women Journansi Television Journabo-21st Nigerian Women.. | wikipedia | yo |
ìsioma NkemdiLim Nkírúka Daniel (Bii ní 1981) jẹ oniroyin ọmọ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O fi esi si iroyin nipa obinrin ti o rewa julo ni agbaye, eyi lo fa ti awon ki awon Musulumi fi so wipe ki won pa.Isioma lo si ile eko giga ti University of Central Lancashire nibi ti o ti gboye ninu iroyin ati oselu ni odun 2001.. | wikipedia | yo |
Ó bèèrè iṣẹ́ ìròyìn ní Thisday tí ó n ṣe ìwé ìròyìn jáde ní ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹrìn dínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2002, ó fi èsì sí ìtako àwọn Mùsùlùmí nípa ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ní àgbáyé tí wọ́n fẹ́ ṣe ní ọdún yẹn.. | wikipedia | yo |
O sọ wipe awon Musulumi so wipe ko dara ki won ko awon obinrin méjìlélọ́gọ́rùn papo lati wo eni ti o dara ju lọ, o ni pe ka ni Mohammed wa laye ni, o ma mu ikan lara awon obinrin naa fi se aya.. | wikipedia | yo |
Oro yi lo fa ija esin ti o pa eyan to le ni igba, ti awon egberun eyan si farapa, opolopo awon eyan si padanu ile won.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dáná sí ilé iṣẹ́ Thisday ní Ìpínlẹ̀ Kaduna lẹ́yìn tí ilé iṣẹ́ náà ti ìkò.Daniel fi ilé iṣẹ́ ìwé ìròyìn náà sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì, ó sì lọ sí orílẹ̀ èdè Benin.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kerindinlogbon osu Kọkànlá odun 2002, ijoba Musulumi so wipe ko si ese ti enikeni ba pa Isioma Daniel.. | wikipedia | yo |
Igbá keji Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Zamfara, mamuda Aliyu Shinka sọ wipe ti Musulumi kan ba ri Isioma Daniel, pe ki won pa, pe ise esin ni won se pe ko si ese nibe.. | wikipedia | yo |
Akọ̀wé àgbà ti Nigerian Supreme Council for Islamic Affairs, Lateef Adegbitẹ sọ wípé ki wọ́n ma tẹ̀lé ìdájọ́ pe ki wọ́n pa Daniel, nítorí ko kin ṣe Musulumi, bẹ́ẹ̀ni ilé iṣẹ́ ìgbéròyìn jáde náà ti bẹ̀bẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni 1981Àwọn Ènìyàn Aruwádìí of the University of Central Lancashirelosiswa-related controversies exPatria in the United Kingdom Kingdom Zbre Fromtime Lagos LagosNigerian Refugeesplace of Birth Missing (Living People) Women Journad-Century Journalists.. | wikipedia | yo |
Abike kafàyat oluwa Tóyìn dàbíri-eréwá jẹ́ òṣèlú àti ọmọ ẹgbẹ́ tẹ́lẹ̀ fún Nigeria Federal House of Representatives, òun sì ni aṣojú fún ìlú Ikorodu ti Ìpínlẹ̀ Èkó níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
Òun sì ni alága tẹ́lẹ̀ fún ìgbìmọ̀ diaspora Affairs.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó di olùrànlọ́wọ́ pàtàkì àgbà fún olórí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari lórí ọ̀rọ̀ àjèjì.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù kọkànlá ọdún 2018, ó di Alátọ́ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí ó wà ní diaspora Commission.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ olùfọwọ́sí fún together Nigeria, tí ó jẹ́ ètò tí wọ́n gbé kalẹ̀ láti lè ṣí ṣe kí Buhari lè wọlé gẹ́gẹ́ bíi olórí orílẹ̀ èdè ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
O gboye ninu ede Gẹẹsi ni ile eko giga ti University of Ife.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Lagos níbi tí ó ti gboyè Masters nínú Mass Communication.Iṣẹ́ dàbírí sì ṣe pẹ̀lú Nigerian Television Authority (NTA) fún ọdún mẹ́ẹ̀dógún, ó sì ṣe atọ́kùn fún àwọn ètò ìròyìn pàápàá jù lọ ní pa iṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Oun ni Alaga fun Igbimọ Media ni Federal House of Representatives lati ọdun 2007.Awon itọkasi awon eniyan AlààyèYoruba Women in PoliticsPeople From JoSobafe Awólọ́wọ̀ University alumniUniversity of Lagos alumniJohn f.. | wikipedia | yo |
Kennedy School of Government Ibidọ́gba-Century Nigerian Women Polimembers of the House of Representatives (Nigeria)Year of Birth Missing (Living People)Women in Lagos PoliticsNigerian Women Journals Journals Television Journansi Television Journalists.. | wikipedia | yo |
Òun ní alátúnṣe fún ilé iṣẹ́ slow Travel Stockholm.. | wikipedia | yo |
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ti farahàn nínú National Geographic Heltì, BBC àti CNN.Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ò gbé ní Èkó ní Nàìjíríà nígbà di ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún tí ó wá fi lọ sí orílẹ̀ èdè United States of America.. | wikipedia | yo |
Ó gboyè master's nínú Information System ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Maryland.. | wikipedia | yo |
Ní ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún, wọ́n mú ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Oxford, ṣùgbọ́n kò lọ nítorí kò rí owó san.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2006, ó lọ sí orílẹ̀-èdè Sweden pẹ̀lú ọkọ rẹ̀.Isẹ́ ó béèrè iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi oníròyìn orí pápá ní Rív-Challenge.. | wikipedia | yo |
Ó sì ṣe fún ọdún méjìlá pẹ̀lú Gis kí ó tó di ògbóǹtarìgì ayàwòrán.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2006, o darapọ mọ Matador Network gẹgẹ bi alátúnṣe.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2011, ó kópa nínú ìdíje ti Quark Ibimọla gbé kalẹ̀ láti lè mú akọ̀wé tí ó ma lọ sí ọ̀pọ̀ tí ó wà ní àríwá láti lẹ̀ lọ kọ ìtàn nípa rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó kópa nínu eré tí wọ́n sá ní Fiji.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Amarachi Nwosu (bíi ní Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kesan Ọdún 1994) jẹ́ Ayàwòrán, elere àti Akọ̀wé.. | wikipedia | yo |
Eré ìtàn, Black in Tokyo tí ó ṣe ti farahan ní International Centre of Photography ní ọdún 2017 ní ìlú New York , ó sì ti farahan ní Ultra Super New Gallery ní ìlú Harajàku.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ àwọn Obi Amarachi jẹ́ ọmọ ibo.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Temple University ní ilẹ̀ Philadelphia.Iṣẹ́ ní ọdún 2019, Maalami Yousafza tí ó gba ẹ̀bùn Nobel Laureate Turugest Ríte pee Nwosu láti ya àwọn àwòrán ní ìrìnàjò rẹ̀ sí Tokyo.Òun ni ó ya àwòrán fún àwọn èyàn gbájúmọ́ bíi Naomi Campbell nígbà tí ó wá sí ìlú Èkó ní Nàìjíríà àti Ẹbọnée Davis.. | wikipedia | yo |
O si ti ṣe adari fun awọn ere kekere fun awọn ile ise bii Nike ni Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó ti sí ṣe pẹ̀lú àwọn olórin bíi Mr EAzi, Yxng bane, Nonso Ámádì, Arapìtàn the Selemáyà, Santi, Kwẹ̀sì Arthur àti tóbi Lou.. | wikipedia | yo |
O sì ṣe gégé bíi ayaworan fún Childish GamBin ní ọdún 2018.. | wikipedia | yo |
Òun ni ayàwòrán fún ètò The Fader tí wọ́n ṣe ní orílẹ̀ èdè Japan.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, òun àti Stella McCartney jọ ní àríyànjiyàn.àwọn Ìtọ́kasí àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Muma gee ( née Wwame; bi 18 November 1978), agbẹjọro Mo bi Muma gẹ́ẹ́ ( /M U M əə Gd Mo / ), afi "Ṣe rere gigi", ni a Nigerian singer-sile, oṣere, Businesswoman, njagun onise, tẹlifisiọnu eniyan ati oloselu.. | wikipedia | yo |
itọwo akọkọ ti ùwame ti Stardom wa nipasẹ orin rẹ "kádé", eyiti o di orin akole akọle awọ-akoko akọkọ rẹ, ti a tu silẹ ni ọdun 2006.. | wikipedia | yo |
Ẹyọ ẹlẹgbẹ ti orin ti o tẹle pẹlu wudi awa, ti gba awọn iforukọsilẹ marun, pẹlu meji lati awọn Awards àjọyọ̀ (aworan ti o dara julọ ati aṣọ ti o dara julọ) ati ọkan kọọkan lati awọn aṣayan fidio orin orin Nigeria, Awọn Awards Olori, ati Awọn Awards ohun orin orin City.,ni ibẹrẹ aye bibi ni Port Harcourt, Ipinle Rivers si Awọn obi ti Ẹpe ẹgbẹ ti ẹya Igbo, ùwahu dagba ni idile Kristiẹni ti o muna, kẹta ti ọmọ mẹfa.. | wikipedia | yo |
bàbá rẹ̀, tí ó kópa nínú òògùn ológun, kú nígbàtí ó jẹ́ ọmọdé.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ mẹrin, ó darapọ̀ mọ́ akọrin agbègbè ní ilé ìjọ́sìn rẹ̀, Adventist-ọjọ́ Adtakoth .. | wikipedia | yo |
Ó wà níbẹ̀ pé ó bẹ̀rẹ̀ láti mọ talẹnti orin rẹ̀ ati agbára rẹ̀.. | wikipedia | yo |
nígbàtí ó parí ètò-ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ àti ilé-ẹ̀kọ́ giga rẹ ni ìlú Àbújá, Ùwahu forúkọsílẹ̀ ní University of Port Harcourt ó sì gba àdun kan ní Arts Theatre .. | wikipedia | yo |
Ní àfikún sí ìpìlẹ̀ ẹ̀kọ́ ìmọ̀-èrò rẹ, ó ní àti ṣíṣe ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìṣọ̀wọ́ mìíràn pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ yíyalo ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, ilé oúnjẹ, ṣọ́ọ̀bù télọ̀ àti ilé ìṣọ́ ẹwà.. | wikipedia | yo |
ó tún di apákan ti ibi orin Burgeoning ti Port Harcourt, ṣiṣẹ́ ní àwọn ile-alẹ alẹ àti àwọn ìfi sí inú ìlú .Ìgbésí ayé ara ẹni gánù ngbé ní Port Harcourt pẹ̀lú ọkọ òṣèré rẹ̀, ẹnití ó ti ní ayọ̀ pẹ̀lú ìyàwó láti ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
Awọn mejeeji jẹ Kristian Olùfọkànsìn ati ko ṣe alabapin ninu igbeyawo ni o di ọjọ 18 Oṣu Kẹrin ọdun 2014, wọn ni awọn ọmọ meji, marun ati ọmọbinrin ibeji, eyiti wọn darukọ Chika ati Chisa èké.. | wikipedia | yo |