cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Wọ́n ń lo ìmọ̀ ìdàgbà-sókè ìmọ̀-ẹ̀rọ àgbẹlẹ̀ ró (àì) láti articial ma fi ṣàwárí àwòrán àwọn 3ni tí wọ́n ti lùgbàdì àrùn yí nípa lílo àwọn ọ̀nà(CT).Àwọn ìtọ́kasíàwọn ìmọ̀ nípa COVID-19 tí ó ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Àjàkáyé-àrùn (Panmia láti inú èdè Greek tó túnmọ sí "Gbogbo" àti "Ènìyàn") jẹ́ Ìwsókè àkóràn àrùn kan tí ó nlọ kaa kiri orílẹ̀-èdè tàbí ẹkùn tí ó jù ẹyọ̀kan lọ..
wikipedia
yo
We tànkálẹ̀ àrùn láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn ní agbègbè tàbí ẹkùn fún ìwọ̀nba ìgbà díẹ̀ ni wọ́n npè ní "Àjàkálẹ̀-àrùn” (Yíya)..
wikipedia
yo
ìtànkálẹ̀ àrùn tí ò jẹ wípé o ní iye ìwọ̀nba àwọn ènìyàn tí wọ́n kọ́ ọ ni wọ́n ń pè ní "en. Kì í ṣe àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé..
wikipedia
yo
Arun enilàun ti o je wipe o ni iye awon eniyan ti won ko o ti ki i se wipe o tan kaa kiri bi ajakale-arun ti o ma n seyo ni akoko ni a le ya soto nitori pe awon arun bayi i ma n waye leekanna ni awon ẹkun ti o tobi ni agbaye sugbon won ki i ran kaa kiri agbaye.itunmo ati ipele-arun tokari-aye je ajakale arun ti o n tan kaa kiri gbogbo agbaye..
wikipedia
yo
A kò lè pe àrùn tabi àìsàn kan ní àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé nítorí pé ó wà káà kiri tabi pé ó ń pa ọ̀pọ̀ eniyan; àrùn yí gbọdọ̀ jẹ́ àkóràn..
wikipedia
yo
Fun àpẹrẹ, arun jẹjẹrẹ jẹ́ àrùn kan ti o n pa ọpọlọpọ eniyan ṣugbọn a ko le pe e ni ajakale-arun tokari-aye nitori pe ki i se arun àkóràn tabi arun ti o le ran eniyan.Àwọn oṣuwọn ti ajakale-arun fi ma ń ran (nibayi ajakale-arun tokari-aye) ma n wá sókè wá sílé ti a bá gbé e sí ori awonya lati fi han iye awon eniyan ti won ti fi ara ko arun yi ni akoko kan..
wikipedia
yo
Ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni lílọ sókè wá sílé àjàkálẹ̀-àrùn yí ma ń wáyé ní àkókò tí àjàkálẹ̀-àrùn yí bá ń ràn káà kiri..
wikipedia
yo
A\wọn àrùn àkóràn ma ń sábà a tànkálẹ̀ ní ìpele mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú àwọnyà ìsàlẹ̀ yí.Ìpele ìkínní ṣẹlẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ohun tí ó tẹ̀ yí..
wikipedia
yo
Tí a bá lọ ìkálẹ̀jú àjàkálẹ̀-àrùn erankowo gẹ́gẹ́ bi apẹẹrẹ, eleyí ma a jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ìfẹsẹ̀-àrùn yí-àrùn yíní nígbàtí wọn bá ìdí ìlà ìsẹ̀lẹ̀ díẹ̀ múlẹ̀.ìpele kejì ohun tí ó tẹ̀ yí ń ṣàlàyé lórí àjàkálẹ̀-àrùn “ìpele agbègbè.
wikipedia
yo
Èyí ma ń wáyé nígbàtí àkóràn àrùn láàrín àwọn ènìyàn bá ṣe ń pọ̀ sí bí àwọn ènìyàn tuntun ṣe ń kó àrùn yí.Ìpele kẹta Ohun tí ó tẹ̀ yí ń ṣe àfihàn pé wọn kò ì ti kápá ìbújáde àjàkálẹ̀-àrùn yí tàbí pé ó ṣe é ṣe kí àkóràn àrùn tuntun má sì rárá.Ìṣàkóso lòúnka àwọn Ìgbésẹ̀ ní àwọn ìpínlẹ̀ lè gbé láti dínwó ìbújáde àjàkálẹ̀-àrùn tó-kárí-ayé kù..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, Àjọ tí ó ń rí sí ètò Ìlera ní Àgbáyé, World Health Organization ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ìlànà ètò ìlera káríayé, èyí tí í ṣe ìlànà òfin kan tí yíò ṣe ìdíwọ́, ìdarí, àti ìjigírì sí ẹ̀wù ìlera gbogbo ènìyàn tí ó ṣe é ṣe kí ó tànkálẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè..
wikipedia
yo
Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé, World Health Organization tún ṣe àgbékalẹ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé aláfọwọ́kọ kan láti kojú àwọn àjàkálẹ̀-àrùn..
wikipedia
yo
Àlàyé aláfọwọ́kọ yí ni wọ́n kọ́kọ́ ṣe àtẹ̀jáde rẹ ní ọdún 1999 tí wọ́n sì ṣe àtúnwò àti imudojuìwọ̀n rẹ ní ọdún 2005 àti ọdún 2009..
wikipedia
yo
Eyi ti o poju lo ninu awon ilana ti won lo lati fi koju ajakale-arun korona ni won mu jade lati inu awon ilana eto ilera ti agbaye ti odun 2005 ati awon itọsọna igbaradi fun ajakale-arun ti o je ti ajo ti o n ri si eto ilera ni agbaye, World Health Organization.àpérò nla kan ti waye lori ilana "t" meta (Testing, Treat and Tracing) eyi ti o gba awon orile-ede laaye lati se ayewo orisirisi awon isele ki o to di wipe won ya won soto fun itoju..
wikipedia
yo
Ìlànà yí ló ní ṣe pẹ̀lú wíwá gbogbo ènìyàn tí ẹni tí ó ti fi ara kó àrùn yí ti ṣe alabapade pẹ̀lú káà kiri kí wọ́n sì yà wọ́n sọ́tọ̀..
wikipedia
yo
Ìlànà yí jẹ́ èyí tí wọ́n mọ̀ kaa kiri nítorí àgbékalẹ̀ rẹ̀ tí ó dijú ní àwọn orílẹ̀-èdè bí I South Korea àti Singapore, bíótilẹ̀bí àwọn orílẹ̀-èdè yí tí wà ní Ìmúrasílẹ̀ tí ó dára pẹ̀lú àwọn oríṣiríṣi ìlànà lọ́mba tí SARS ti FA tí fa-ẹni tàbí ní ní kukuruna sí ara ẹni jẹ́ àgbékalẹ̀ fún ìlera gbogbo ènìyàn lati mú kí àrùn àkóràn dínkù nípa ṣiṣẹ́ tí àwọn ènìyàn lati sunmo ara wọn nítorí àrùn ja ọmọ tí àwọn àìsàn tí ó lè ran wọn..
wikipedia
yo
Ryan ti àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé, World Health Organization sọ níbi àpérò kan ní Oṣù Kẹta ọdún 2019 pe Ení-síra-ẹni “jẹ́ ìlànà fún ìgbà díẹ̀ láti dín owó kátàn erankorona yí kú ni ṣùgbọ́n kì í ṣe láti mú ìyanjú wá sí ìṣẹ̀lẹ̀ erankorona..
wikipedia
yo
Lóòtọ́ ló jẹ́ wípé ìlànà yĩ jẹ́ ìlànà tí ó ná ni lọ́wọ́ ṣùgbọ́n a gbọ́dọ̀ lò ó pẹ̀lú àwọn ìlànà míràn láti wá ìyànjú sí ìṣòro yĩ..
wikipedia
yo
Dókítà Riyan sọ kedere pé Ebàá-síra-ẹni kò lè mú àrùn yí kúrò.Àwọn àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé tí ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́HIV/AIDS Àjọ tí ó ń rí sí Ètò Ìlera ní Àgbáyé, World Health Organization lo àkọlé “Àjàkálẹ̀-àrùn Àgbáyé” láti fi ṣe àpèjúwe HIV, àrùn yí jẹ́ àjàkálẹ̀-àrùn tí ó ń tẹ̀lé ìtunmọ̀ ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Láti bí i ọdún 2018, ó tó 37.9 million àwọn ènìyàn tí wọ́n ti fi arakó àrùn HIV ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
Awon eniyan ti o to 770,000 ni o ti je alaisi latipase arun AIDS ni odun 2018..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́lọ́wọ́, Ẹkùn tí ìṣẹ̀lẹ̀ yí ṣẹlẹ̀ sí jù ní iha ìsàlẹ̀ aṣálẹ̀ Sahara ní ilẹ̀ Africa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ìfojúsùn àrùn HIV tuntun tí ó tó 61% ni ó ṣẹlẹ̀ ní ẹkùn yí.Àwọn ẹrankoronáàwọn erankorona (CoV) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí àrùn tí ó ń fa àwọn àìsàn bẹ̀rẹ̀ láti orí òtútù títí tí ó fi dé orí àwọn àrùn tí ó lágbára bí í Middle East Yupirátory Syndroms (mers-CoV-irú) àti Severe ACUte Aguritory Synd (SARS-CoV-irú
wikipedia
yo
Eya erankorona tuntun ti o n je (SARS-CoV-2) ni o n fa arun erankorona 2019 tabi COVID-19..
wikipedia
yo
Díẹ̀ nínú àwọn erankorona ní zOonitic, èyí tí ó túnmọ sí wípé wón ma ń ṣe àtàgbà láàrín àwọn ẹranko àti àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
Àyẹ̀wò kíkún fi yé wa wípé SARS-CoV jẹ́ èyí tí ó ti ara Ológbò Civetí civet cats jáde wá sí ara ènìyàn, àti wípé mers-CoV jáde wá láti ara ràkùnmí wá sí ara ẹ̀dá ènìyàn..
wikipedia
yo
Opolopo awon erankorona ti a mo ni won wa kaa kiri ninu awon eranko ti won ko i ti ran mo eda eniyan.Ìwọ̀n erankorona tuntun kan eyi ti ìpìlẹ̀ re bere ni Wuhan, ni igberiko hubei, ni orile-ede China, ni opin osu kejila odun 2019 ti fa oniruuru isele arun ti ategun n gbe kiri ti won n tọka si gege bi i arun erankorona 2019 (COVID-19)..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi Johns Hopkins University Dashboard, ó fẹ́rẹ̀ ẹ́ to igba(200) Àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn agbèègbè tí ìṣẹ̀lẹ̀ COVID-19 ti ṣẹlẹ̀ sí, pẹ̀lú àwọn ibujade tí ó Deleïko tí ó ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè United States, Central China, Western Europe, àti Iran..
wikipedia
yo
Ni ojo kokanla osu keta odun 2020, ajo ti o n ri si eto ilera ni agbaye, World Health organization se apejuwe itankale arun COVID-19 gege bi i ajakale-arun tokari-aye..
wikipedia
yo
Láti ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 2020, iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti kó àrùn erankorona ní àgbáyé ti to 2.63 Millino, iye àwọn tí wọ́n ti jẹ́ aláìsí ti tó 184.249 àti iye àwọn aláìsàn tí wọ́n ti gba ìwòsàn jẹ́ 722.0.àkíyèsí. àwọn ibesílẹ látirí ìru jẹ àrùn tí ó wà ní ibigbogbo ní ẹkùn PICdínlọ́gbọ̀n àti Subughton tí ó fi mọ́ àwọn apákan ní orílẹ̀-èdè America, Asia àti Africa..
wikipedia
yo
Ní ọdọọdún, ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn ibà tí ó má ń ṣẹlẹ̀ má ń súnmọ́ 350-500 million..
wikipedia
yo
Àtakò òògùn jẹ́ ìṣòro tí ó ń gbèrú sí i nípa ìtọ́jú àrùn ibà ní ọ̀rúndún kọkànlélógún (21st Century) nígbàtí ó jẹ́ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ oògùn ìba ni kò ṣiṣẹ́ mọ́ déédé yàtọ̀ sí Artemisns.arun iba wọ́pọ̀ ní ìgbàkan ní àwọn apá ilẹ̀ Europe àti ní àríwá America níbití ó jẹ́ wípé kò sí ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn yí mọ́ báyĩ ..
wikipedia
yo
O ṣe e ṣe ki o jẹ wipe arun iba yi lọwọ ninu iṣubu ile ọba Róòmù (Roman Empire)..
wikipedia
yo
plasetídò flacipa je n kan ti o di irokeke gidi si awon amunisin ati awon eniyan ilu bakanna nigbati won se afihan re si aarin awon Americas pelu Iṣowo Erusha.Àìsàn SUsha Spanish (ti o waye ni odun 10 si odun 1920) je àkóràn arun ti o ran awon eniyan ti o to 500 million ni gbogbo agbaye pelu awon eniyan ti o wa beerena jinjinna bi i Pacific Islands ati Arctic ti o si ti pa awon eniyan bi i ogun si ogorun un Archls (20–200 million
wikipedia
yo
Àìbìkítà sí àjàkálẹ̀ àrùn yí ṣe ikú pa púpọ̀ àwọn ọ̀dọ́ àti àwọn arúgbó pẹ̀lú òṣùwọ̀n ìwàláàyè tí ó pọ̀ jùlọ fún àwọn tí ó wà ní àárín, ṣùgbọ́n àìsàn Spanish yí pa púpọ̀ nínú àwọn àgbà ọ̀dọ́..
wikipedia
yo
Iye ènìyàn tí àìsàn Spanish yí pa ju iye ènìyàn tí ó kú nígbà ogun àgbáyé ìkínní..
wikipedia
yo
Àìsàn yí pa àwọn ènìyàn tí ó pọ̀ ní ọ̀sẹ̀ márùndínlọ́gbọ̀n ju àwọn ènìyàn ti àrùn AIDS pa ní ọdún márùndínlọ́gbọ̀n àkókò..
wikipedia
yo
Whilepo àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ogun àti ibi gbogbo tí ó súnmọ́ ara wọn nígbà ogun àgbáyé ìkínní ló fà á kí ìtànkálẹ̀ àrùn yí po nítorí àìlágbára àwọn ọmọ jagunjagun lórí àìsàn yí lè jẹ́ ó ùn tí ó pọ̀ nítorí aápọn, àìní ìtọ́jú, àti ìkọlù pẹ̀lú kemikali..
wikipedia
yo
Ètò ìrìnnà tí ó dára sì jẹ́ kí ó tún rọrùn fún àwọn jagunjagun, àwọn atukọ̀ àti àwọn ará ìlú tí ó ń rìnrìn àjò láti tan àrùn yí káà kiri.ìkọminú nípa ọjọ́ iwájú àwọn kòkòrò àrùnòògùn apakòkòrò tó ń dènà àrùn àwọn oògùn apakòkòrò ni wọ́n ma ń sábà á tọ́ka sí nígbàmíràn gẹ́gẹ́ bí i "SuperBus",
wikipedia
yo
Ó ṣe é ṣe kí wọ́n tún kó ipa lórí i bí àwọn àrùn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń kápá lọ́wọ́lọ́wọ́ tún ṣe ń fara hàn..
wikipedia
yo
Fun àpẹrẹ iṣẹlẹ ìkòọfẹ̀ẹ̀ eyi ti agbara ọna iwosan rẹ ko sise mo je n kan ti o n kan awon onimo nipa eto ilera lobere.O fẹrẹ to idaji Archls awon isele tuntun ti o je ti Multi-Mégbe tuberculosis (DR-BBB) ti WN fojusun pe o n sele ni ọdọọdun kaa kiri ..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè China àti ti India ni wọ́n ní òṣùwọ̀n ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ga jùlọ nípa Mulpínrug-resi- BB..
wikipedia
yo
Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé sọ wípé ó fẹ́rẹ̀ súnmọ́ 50 million àwọn ènìyàn ní àgbáyé tí wọ́n ti kó àrùn Mdr-BB pẹ̀lú 79% àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yí tí àwọn òògùn apakòkòrò bí i mẹ́ta tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ kò ṣiṣẹ́ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, àwọn ìsẹ̀lẹ̀ MDR-T tí ó tó 124 ni wọ́n kéde wọn ní orílẹ̀-èdè America.OloLYly Drug-Mégbe tuberculosis (XDR BT) ni wọ́n ṣe ìdánimo rẹ̀ ní ilẹ̀ Africa ní ọdún 2006, lẹhinna ni wọ́n ṣe àwárí rẹ̀ pé ó wà ní ọ̀kàndín (49) orílẹ̀ èdè tí ó fi mọ́ ilẹ̀ America..
wikipedia
yo
Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ,World Health Organisation ṣe ìṣírò rẹ̀ pé ìṣẹ̀lẹ̀ Xdr-BB tí ó tó 40,000 ni ó ń ṣẹlẹ̀ ní ọdún .Fún bí i ogún ọdún sẹ́yìn, àwọn kòkòrò àrùn tí ó wọ́pọ̀ ní staphylococcus, opó, ṣeérratia Marcese àti kokoRíd tí ó ń fa àtakò sí onírúurú oògùn apakòkòrò bí i Vanywù, àti gbogbo àwọn oògùn apakòkòrò bí i Àmínóyly àti cephalos Popo..
wikipedia
yo
Àwọn kòkòrò tí ó ń gbógun ti àwọn òògùn apakòkòrò jẹ ọ̀kan lára àwọn ń kan tó ń fa àwọn àrùn tó ní í ṣe pẹ̀lú ìlera..
wikipedia
yo
Ní àfikún, àwọn àrùn tí ó ń gbógun ti oògùn apakòkòrò bí i Méthi-resi-kudiẹ staphylococcus aureus (MSafe) tí ó jẹ́ wípé wón gbìnlé ní ń kàn bí i ọdún mélo ó kàn sẹ́yìn, ń ṣe àkóbá fún ẹni tí ó ti ní ìwòsàn tẹ́lẹ̀.Àwọn kòkòrò ìbá ti ń sọ ẹ̀jẹ̀ di omiiba sẹ̀jẹ̀domi (ôn Hemoràkókò Fever) jẹ́ àwọn àrùn tí ó ma ń ràn gidigidi tí wọ́n sì ń ṣe Ikúpani..
wikipedia
yo
Àwọn àpẹẹrẹ ni Ebola, Lassa, Rift Valley, Marburg àti Bolivan Hemorrhagic..
wikipedia
yo
Àwọn àrùn yí ní agbára láti pé kí wọ́n di àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé..
wikipedia
yo
Agbara ti awon arun yi ni lati tete tànkálẹ̀ di ajakale-arun tokari-aye ko po rara nitoripe titankale won ma nilo ifarakanra pelu eniti o ti ni arun yi tele sugbon eniti o ni arun yi tele ko ni akoko pupo rara ti yio fi je alaisi tabi ki o rin aisan to lagbara..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nba àkókó tó wà láàrin ẹnití ó ní àrùn yí àti ìgbátí àmì àrùn yí ma fi ara hàn ma ń fún àwọn dókítà láàyè láti lè tètè fi ẹni bẹ́ ẹ pamọ́ kí wọ́n sì dí i lọ́wọ́ láti má bá a gbé àrùn yí lọ sí ibòmíràn.Kòkòrò Zikaìbújáde kòkòrò Zika bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2005 tí ó sì ń tẹ̀síwájú kíkankíkan ní gbogbo ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2016 pẹ̀lú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ju 1.5 million lọ jákè jádò àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ju méjìlá lọ ní ìlú America..
wikipedia
yo
Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé, World Health Organization ṣe ìkìlọ̀ pé àrùn Zika ní agbára láti di àjàkálẹ̀-àrùn tí yio tàn ká gbogbo àgbáyé tí wọ́n kò bá tètè dènà rẹ̀.Ìtọ́kasí àjàkálẹ̀-àrùn ìmọ̀ ìmọ̀ nípa COVID-19 tí ó ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Onírúuru aba lori wiwo iboju nigba ajakalẹ aarun kariaye erankorona odun 2019 lati owo awon elétò ati ajo ilera ati awon ijoba..
wikipedia
yo
Àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization, WHO àti àwọn elétò ìlera àwùjọ gbà pé wíwọ ìbòjú máa ń fa àdínkù rírankalẹ̀ àjàkálẹ̀ ààrùn èémí bí i erankorona ọdún 2019 bí ó tilẹ̀ wù kí ó rí, àkòrí-ọ̀rọ̀ jẹ́ èyí tí ó ti ń fa àríyànjiyàn, láàárín àwọn oníṣẹ́ ìlera kan àti àwọn ìjọba lórí ìlànà wíwọ ìbòjú..
wikipedia
yo
Títí di oṣù karùn-ún ọdún 2020, , ìdá méjìdínláàádọ́rùn-ún, 88% nínú àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn ni àgbáyé ń gbé ní orílẹ̀-èdè tó kàn-án nípa tàbí dá àbá láti lo ìbòjú ní àwùjọ ènìyàn púpọ̀; ìdá márùnléláàádọ́rin, 75 ni àwọn orílẹ̀ èdè tó kàn án nípa láti máa lo ìbòjú..
wikipedia
yo
Àríyànjiyàn ti waye lori pe nje o pọn dandan ki eniyan wọ iboju nigba ti o ba wa ni ẹkún-sira-ẹni láwùjọ niwọn mita meji tabi ẹsẹ̀ bata mẹfa, ati nigba ti eniyan ba n ṣere idaraya..
wikipedia
yo
Ní àfikún, àwọn àjọ elétò ìlera àwọn orílẹ̀-lédè kan àti àwọn agbègbè mìíràn ti yíhùn padà nípa lílo ìbòjú nígbàdégbà..
wikipedia
yo
Ìbòjú ti wá di ohun ọ̀wọ́n nígbà ààrùn erankorona ọdún 2019, gbogbo èyí tí ó wà lóde kọ́ ni wọ́n fọwọ́ sí..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní gugú Sudan tí wọ́n tún ń dá pé ní COVID-19 ni ó kúrí kan ní orílẹ̀-èdè Sudan gúùsù gùn ní Oṣù Kẹrin Ọdún 2020..
wikipedia
yo
Nígbà tí yóò fi di ọjọ́ kẹ́sà oṣù keje, wọ́n ti rí àkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí ó tó ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùún kan ó lé mọ́kàndínlọ́gbọ̀n tí wọ́n ti lùgbàdì àìsàn yí, tí èèyàn mọ́kànlélógójì ti dágbére-fàyè látàrí ìbúrẹ́kẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn yí ní apá Gúsù orílẹ̀-èdèSudan.Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ àti àkókò ìṣẹ̀lẹ̀àwọn ìgbésẹ̀ lórí ìdènà àrùn COVID-19ni ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kejì ọdún 2020, ìjọba ilẹ̀ Gúsù Sudan fòpin sí ìgbòkègbodò ìrìnà ọkọ̀ Òfurufú pàá pàá jùlọ sí orílẹ̀-èdè tí àrùn náà ti pọ̀ lápọ̀jù..
wikipedia
yo
nígbà tí ó di ogúnjọ́ oṣù kẹta, wọ́n tún tì gbog ó ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ títí dé fáfitì gbogbo pa títí di ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹrin..
wikipedia
yo
Igbakeji Aare orile-ede naa, Ogbeni Hussein Abdelbagi paṣẹ pe ki won ti gbogbo Ojúkò Idaraya, Oselu, ati ile ijosin pata pa fun ose mefa gbáko..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn 2yí ni wọ́n ṣòfin kónílé-ó-gbélé láti ọwọ́ agogo mẹ́jọ alẹ́ sí agogo mẹfa ìdajì ọjọ́ keji..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹtadinlọgbọn oṣù kẹta ọdún 2020, wọ́n fi iye eniyan tí ó tó ọrùndínlẹ́gbẹ̀ta sí iyàrá àdágbé, tí pupọ ninu wọn sì sá jáde lọ sí apá àríwá orílẹ̀-èdè náà, tí àwọn wọ̀nyẹn náà sì ti ẹnu ibodè wọn pa fún ọjọ́ mẹrinla gbáko..
wikipedia
yo
Titi di ojo karùún osu keta titi di ojo karùún osu kerin odun 2020, ti ajakale arun korona ti tan de orile-ede Mali, orile-ede guoba Sudan nikan ni ko tii ni akosile kankan fun arun korona.igbese ti osu kerin odun 2020 ni ojo karùún osu kerin, won se akosile ajakale arun korona ni orile-ede naa lati ara ọdọmọkunrin omo odun mọkandinlọgbọn kan ti o je osise ajo isokan agbayeti o dari wale lati orile-ede Netherlands Ethiopia..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ yí ni ó sì mú kí orílẹ̀-èdè gúsù Sudan ó jẹ́ orílẹ̀-èdè kọkànlélọ́gọ́ta ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí ó ti ní àkọsílẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn korona..
wikipedia
yo
Wọ́n fi aláárẹ̀ náà sínú ilé gbégbé akátá àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé, tí wọ́n sì ṣe ìwádí nípa iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti súnmọ́ aláárẹ̀ náà.Àkọsílẹ̀ èkejì ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin yí kan náà tí ẹni tó tún fara káṣà àrùn náà tún jẹ́ ìkan nínú àwọn òṣìṣẹ́ àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé tí ó jẹ́ obìnrin tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju ọdún kanọ̀ lọ tí òun náàbkàb’’ láti orílẹ̀-èdè Nairobi ní ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹta tí ó sì fi ara rẹ̀ sínú ìyàrá adágbé kí àrùn náà ó má ba tán jù bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ ẹnì kẹta ni obìnrin kan tí 9un náà tún jẹ́ ìkan nínú àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé tí ó ti fara kín aláàárẹ̀ àkọ́kọ́..
wikipedia
yo
Ijoba orile-ede guso Sudan fagile–Bíbọ̀ ọkọ ofurufu labele ni ojo ketala osu osu 2020 odun 2020..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ aláìsàn karùún àti ìkẹfà ní ó wáyé ní ọjọ́ kẹtàlétábù àti ọjọ́ karùnlélógún oṣù kẹrin 9dún 2020, tí àwọn tí wọ́n lu gùdẹ̀ àrùn yí jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Gúsù Sudan.Lẹ́yìn tí wọ́n ti rí àkọsílẹ̀ ènìyàn méjìdínlọ́gbọ̀n ní orílẹ̀-èdè yí, wọ́n ṣe àfikún òfin kónílé-ó-gbélé tì.Ó ti bẹ̀rẹ̀ láti agogo mẹ́jọ alẹ́ sí agogo mẹ́fà ìdájí sí agogo méje alẹ́ sí agogo mẹ́fà àárọ̀ ọjọ́ kejì..
wikipedia
yo
tí wọ́n sì fi àyè gba àwọn ilé oúnjẹ kí wọn má tajà wọn déédé, bákan náà ni wọ́n ti gbogbo ẹnu ìloro orílẹ̀-èdè náà pa pinpin..
wikipedia
yo
Orílẹ̀orílẹ̀-èdè Gúsù Sudan ni iye ènìyàn tí ó ń gbé níbẹ̀ jẹ́ mílíọ̀nù mẹ́rìndínlógún lápapọ̀.Oṣù Karùún ọdún 2020 orílẹ̀-èdè Gúsù Sudan bẹ̀rẹ̀ sí sí àwọn ọ̀nà ètò ọ̀tọ̀ ajé wọn gbogbo, wọ́n de òfin kónílé-ó-gbélé lékè láti agogo mẹ́wàá alẹ́ sí agogo mẹ́fà ìdájí ọjọ́ kejì, àwọn kẹ̀kẹ́ alùpùpù wọn náà ń gbèrò tí kò ju ẹyọ kan ṣoṣo lọ tí àwọn méjẽjì sì gbọdọ̀ wọ ìbòjú, àwọn ọlọ́kọ̀ èrò náà ń gbé èrò méjì tí àwọn náà gbọdọ̀ wọn ìbòjú..
wikipedia
yo
Awon ile-itaja gbogbo naa bẹrẹ owo wọn ni pẹrẹu, amo won ko gbọdọ po ju maruun lo ni ojúkò kan soso, bi o tile je wipe ajakale arun korona si wa nigboro sibe..
wikipedia
yo
Wọ́n tún sí àwọn ìyìlé òfurufú gbogbo padà ní 9jo kejìlá Oṣù karùún, ọdún 2020 fún lí-bí labele àti Kari-ayé gbogbo.gbẹgẹdẹ gb̀kan ní ọjọ́ lálálá oṣù Kárùún ọdún 2020, Sudan ní akosile ẹni àkọ́kọ́ tó gbékurù jẹ́ ẹwọ́ látàrí Aare àrùn COVID-19 tí ó ń ja ní orílẹ̀ ní-èdè náà. tí yóò fi di ojo kejidinlogun Oṣù Kárùún náà náà, igbakeji rẹ̀- alágu gugu-ede gugugugu Ma' ma máa maa Iyawo rẹ̀ maa ìyàwó náà lu ẹnu korona..
wikipedia
yo
Ewe, Mínísítà fún ẹ̀tọ́ ìròyìn ìyẹn ọ̀gbẹ́ni Michael Omase loweth àti gbogbo àwọn ìgbìmọ̀ ìfin tí Iye wọn jẹ́ mẹ́ẹ̀dógún tí Ààrẹ Wọn yàn láti wá láti ṣkò sí àjàkájì Àdun Ọt ní orílẹ̀-èdè náà tún ̀n ǹwo yí yí ní ọjọ́ kọkàn oṣù ní ní náà..
wikipedia
yo
kò pé sí àsìkò yí tí igbákejì Ààrẹ mìíràn tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Hussein Abdelbagi fara káṣà àrùn korona òun Oèlú olóríi Amúṣẹ́ṣe fún Ààrẹ ní 9jo kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù karùún Ọdún 2020..
wikipedia
yo
Vice President James wáni Inga announced he had tested positive on May 30.Àwọn itọkasiajakalẹ àrùnajakalẹ àrùn COVID-19 gegebi orile-ede..
wikipedia
yo
Grace àtinúke Oyeludé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrindinlogun oṣù Kọkànlá ọdún 1931, (November 16, 1931) jẹ́ omidan tó rẹwà jùlọ àkọ́kọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 1957.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn erankorona-19 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí COVID-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ní Oṣù Kẹta ọdún 2020.Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀lọ́jọ̀ kejìlá Oṣù Kìíní ọdún 2020 ní Àjọ elétò ìlera Àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé erankorona, COVID-19, ni ó ń fa aisan èémí láàarín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ Who lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019.Iye ìjà ikú àrùn COVID-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severeté ACUte Oroko syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún àti Bebi, ṣùgbọ́n oníwo náà lágbára jù SARS lọ, pàápàá jù lọ Iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀. Ìbú náà láti igba dé dé ẹni àkọ́kọ́ tí wọ́n kéde rẹ̀ pé ó lùgbàdì àrùn náà lórílẹ̀ èdè olómìnira Benin wáyé ní olú-ìlú orílẹ̀-èdè náà, Port-èdè lọ́jọ́ kẹrìndíndì oṣù kẹta ọdún 2020, on..
wikipedia
yo
Lọ́jọ́ kẹta sí ara wọn ni wọ́n, ni wọ́n kéde eniyan keji tó ní àrùn náà..
wikipedia
yo
Lẹsẹkẹsẹ ní orílẹ̀-èdè kéde ìdádúró ìrìnkèrindò ọkọ̀ láti orílẹ̀ èdè mìíràn wá sí orílẹ̀ èdè náà, bákan náà wọ́n yan ìdágbélé tipátipá fún gbogbo àwọn aré tàbí arìnrìn-àjò tí wọ́n bá wọ orílẹ̀-èdè náà gba òfúrufú..
wikipedia
yo
Kódà, wọ́n gba àwọn olùgbé orílẹ̀ èdè Benin ní ìmọ̀ràn láti máa wọ ìbòjú, kí wọ́n sìn sé ara wọn mọ́lẹ̀ àyàfi bí ó bá pọn dandan láti jáde.Àwọn ìtọ́kasíbẹ̀..
wikipedia
yo
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé ilẹ̀ Malawi ní ọjọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 2020.Ipileta ọjọ́ kejìlá Oṣù Kíní Ọdún 2020, àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé, World Health Organization fìdí rẹ múlẹ̀ pé àrùn korona ni ó fa àìsàn atégùn níbi àjọjọ àwọn ènìyàn ní Wuhan, agbègbè Hubeí, ní orílẹ̀-èdè China èyí tí wọ́n ròyìn rẹ̀ fún àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá ọdún 2019.Ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 kéré púpọ̀ sí ti SARS tí ó wáyé ní ọdún 2003, ṣùgbọ́n ìtàn rẹ̀ pọ̀ gidigidi tí a bá wo àwọn tí ó ti di olóògbé.Àkójọpọ̀ Àkọ́kọ́ oṣù kẹrin ọdún 2020-èdè Mamọ́-èdè Peter Mutrika fìdí ìsẹ̀lẹ̀ mẹ́ta àkọ́kọ́ lóri tí àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 múlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Mawìwì ní ọjọ́ kejì oṣù kẹrin..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́ta yí ni ti arábìnrin kan, ọmọ orílẹ̀-èdè Màláwì tí wọ́n bí sí ilẹ̀ Asian, pẹ̀lú ìbátan rẹ̀ àti ọmọ ọ̀dọ̀ wọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti orílẹ̀-èdè Indian.Ìṣẹ̀lẹ̀ kẹrin ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin èyí tí ó ní ṣe pẹ̀lú ẹnìkan tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà dé láìpẹ́ láti ilẹ̀ Aláwọ̀funfun (United Kingdom)..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ karun ún ni ti arábìnrin kan tí ó ti padà dé láti ilẹ̀ aláwọ̀funfun (United Kingdom) tí wọ́n sì ti yà sọ́tọ̀ fún ọ̀sẹ̀ Melo ó kàn sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ni ojo keje osu kerin ni won kede pe arabinrin yi ti je alaisi..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Màláwì tún ṣe àwárí ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́ta míràn tí ó dájú èyí tí ó mú kí àpapọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn yí di mẹ́jọ..
wikipedia
yo
Okan ni eni odun merinlelogbon kan ti o ti koko ni ifarakanra lesekese pelu eni ti o ti koko fi Rara fun isele arun yi ni ojo keji osu kerin..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ kejì ní ti Ọ̀dọ́bìnrin ọmọ ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n tí ó padà dé láti ilẹ̀ aláwọ̀funfun (United Kingdom) ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹta nígbà tí ìsẹ̀lẹ̀ kẹta jẹ́ ti arákùnrin ọmọ ọgbọ̀n ọdún kan tí ó rin ìrìnàjò lọ sí apá ilẹ̀ Gúúsù ti Áfríkà (South Africa) ní ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹta.Ní Oṣù yí, ìsẹ̀lẹ̀ mẹtadinlogoji(37) ni wọ́n fìdí e múlẹ̀, àwọn ènìyàn mẹ́ta jẹ́ aláìsí nígbàtí àwọn ènìyàn méje gba ìwòsàn, ó wá ku ènìyàn méjì(27) tí àrùn yí sí n bá lọ́wọ́lọ́wọ́.Oṣù karùn ún ọdún 2020ní Oṣù Karun un ìsẹ̀lẹ̀ tuntun tuntun òjìlénígba lé méje(247) ní ó ṣẹlẹ̀, èyí tí ó mú kí iye àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí wọ́n fìdí ẹ múlẹ̀ di orin lé mẹ́rin (284)..
wikipedia
yo
Aláìsàn kan kú, èyí tí ó mú kí àwọn ènìyàn tí ó ti kú di mẹ́rin..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan n po si lati marundinlogoji(35) lo si mejilelogoji(42), o wa ku òjìlénígba din meji(238) awon eniyan ti won n se aisan lowolowo ni ipari osu yi.osu kefa odun 2020ni osu kefa, isele tuntun 940 ni o sele, eyi ti o mu ki iye awon ti won ti fidi e mule pe o ni arun yi di 1224..
wikipedia
yo
Awon alaisan ti won ti gba iwosan n po si lati NAP din meji(218) si otalenigba(260), o wa je wipe 950 awon eniyan ni won n se aisan lowolowo ni ipari osu yi.osu keje odun 2020isele tuntun 2854 ni o seyo ni osu keje, eyi ti o so apapo iye isele ti won ti fidi re mule di 4078..
wikipedia
yo
Iye àwọn aláìsàn tí ó ti kú lọ sókè láti ỌGỌ́RÙN ún(100) sí mẹ́rìnléláàdọ́fà(FAX)..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti ri iwosan gba lo soke si i lati 1615 si Germany, eyi ti o mu ki iye awon alaisan ti o n gba itoju lowolowo je 2089 ni opin osu keje (eyi ti o lo soke pelu ida a ogofa(120) ninu ogorun un (120%) lati opin osu kefa).osu kejo odun 2020ni ojo kejo osu kejo, iye awon alaisan ti ara won ti bọ̀sípò ti rékọjá ida a aadọta ninu ogorun un(50%) fun igba akoko.igbese ijobapelu bi ko ti se si isele ti won fidi re mule ki o to di ojo keji osu kerin, Aare muTharika kede ajakale arun erankorona gege bi i àjálù ti o de ba orile-ede won..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìgbésẹ̀ tí wọ́n gbé kalẹ̀ ni fífagilé àwọn àpéjọ tí ó bá ti ju ọgọrun un eniyan lọ ní àwọn ilé ìjọ́sìn, àwọn ibi àpéjọpọ̀, àwọn ibi igbeyawo ati àwọn ibi ìsìnkú..
wikipedia
yo
Ààrẹ tún sọ wípé kí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ìjọba àti ti aládàáni di tìpa láti ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta..
wikipedia
yo
Ó tún tẹ̀síwájú láti rọ ìjọba pé kí wọ́n dáwọ́ gbígba àwọn àlejò láti òkè-òkun fún àwọn ìpàdé dúró, nígbà tí ó tún fi òfin de àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba láti lọ sí àwọn ìpàdé ní àwọn agbègbè àti òkè-òkun..
wikipedia
yo
Ààrẹ tún rọ àwọn olùgbé ìlú àti àwọn àlejò tí wọn ń bọ̀ láti àwọn orílẹ̀-èdè tí àrùn yí ti ń jà lọ́wọ́lọ́wọ́ pé kí wọ́n fi ara wọn sílẹ̀ fún ìfinípamọ́.Lẹ́hìn ìgbàtí wọ́n ti rí àrídájú lórí ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́rin àkọ́kọ́ ní oṣù kẹrin ni Ààrẹ Mutrika ti gbé àwọn ìgbésẹ̀ tuntun nípa dídá àwọn ìpàdé, àwọn àpéjọ,àti àwọn àpérò dúró..
wikipedia
yo
O tun paṣẹ fun ẹka ti o wa nipa akoso ogba ewon ati ti ile awon omo alàìgbọràn lati pese akojopo oruko awon ẹlẹ́wọ̀n ati ti àwọn ọmọ aláìgbọràn tí wọ́n se àwọn ese kéékèké pẹlu àwọn tí wọ́n ti lo iye akoko ti o po ninu àkókò tí ó yẹ kí wọ́n lò lórí ẹ̀ṣẹ̀ ìwà ọ̀daràn tí kò pọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀..
wikipedia
yo