cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ọmọ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó wà ní ìlú Kaduna níbi tí ó ti jẹ́ ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ tó peregedé jùlọ láàrín àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ ń jáde lọ́dún náà..
wikipedia
yo
Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Royal Military Academy Shurst níbi tí ó tún ti gba ọ̀pá iyì gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ ológun tó wá láti ilẹ̀ òkèrè..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Royal Military College of Science, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ iṣẹ́ Mona-mọ́ná (Óga Engineering) pẹ̀lú ipò àkọ́kọ́ (first classs-ìtọ́kasí àwọnsẹ́ ológun ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Michelle Marie Pfeiffer (; ti a bi ni Oṣu Kẹrin Ọjọ Ọkàn-din-lọgbọn, ọdun 1958) jẹ oṣere ara ile Amẹrika kan..
wikipedia
yo
Oṣere ti o ni ilọsiwaju ti iṣe iboju rẹ ti kọja ogoji ọdun, o di ọkan ninu awọn oṣere Hollywood to jẹ akosemose to dun yatọ julọ ni awọn ọdun 1980 ati 1990, bakan naa o jẹ ọkan ninu awọn ami ibalopọ olokiki julọ ti akoko naa..
wikipedia
yo
Olugba ti ọpọlọpọ awọn ami ìyìn, o ti gba aami eye Golden Globe kan ati aami eye British Academy Film kan, ni afikun si awọn yiyan fun awọn aami ẹyẹ Academy mẹta ati aami eye Primetime Emmy kan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, wọ́n fún un ní ìràwọ̀ àwòrán fíìmù kan lóri Hollywood Walk of FameÌtọ́kasí.Àwọn òṣèré fíhàn ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Àyọkà yìí ṣe àtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Haiti láti ìbẹ̀rẹ̀ dìdedìde àwọn ará Haiti ní 1791..
wikipedia
yo
Ominíran gangan jẹ́ fífilọlẹ̀ ní 1804.Between 1806 and 1820 Haiti was Divided between the northern state, Renamed Kingdom of Haiti in 1811, and the Southern Republic of Haiti..
wikipedia
yo
Between 1822 and 1844 the Republic of Haiti Ruled over the entire Island of Hispaniola, during the period known as the unidẹni of Hispaniola.Àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ HaitiSaint-LKMgue (1791-1804)first Empire of Haiti (1804-1806) of Haiti (1806-1811-Kingdom) of Haiti (1811-1820)Republic of Haiti (1806-1822)Republic of Haiti during the uniọdún of Hispaniola (1822-1844)Republic of Haiti (1844-1849)Second Empire of Haiti (1849-1859)Republic of Haiti (1859-1957)Republic of Haiti during the duValier dynasty (1957-1986) Presidential rẹ̀ Nuse Constitutional rẹ̀ Died died in offipublic of Haiti (1986-present) InDirect Electio.Otes also History of Haiti Politics of Haiti President of Haiti Prime minister of Haiti list of Prime Ministers of Haiti List of Haitian Consorts of MonaOrílẹ̀ of HaitiHaiti listhe of State..
wikipedia
yo
Shafy Bello ti i ṣe ọmọ bibi orile-ede Naijiria je òṣèrébìnrin àti olórin..
wikipedia
yo
Orin kíkọ ni ó fi kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ níbi tí ó ti farahan nínu orin Seyi Sodimu ti "Love Me jẹjẹ" jẹ àkọ́lé rẹ̀ ní ọdún 1997.Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn ìyòìlú America ní Shafy dàgbà sí tí ó sì ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Àkọlé fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ní eti kẹta tí ó jẹ́ fíìmù Yorùbá..
wikipedia
yo
Ile ọkọ ni Shafy wa pelu omo meji.Ni odun 2012, o se Joanne Lawson ninu fiimu agbelewo kan ti akole re n je Tinsel, o si se Adesùsù ninu taste of Love..
wikipedia
yo
láti ìgbà náà ni Shafy ti farahan ninu fiimu agbelewo Yorùbá àti Gẹẹsi, diẹ lara wọn ni; When Love Rewọlé, gbọ́mọ gbọ́mọ Express ati taste of Love.ààtò àwọn fiimu Jehovahréèms Kẹta Scoreago Love Refaragbọ́mọ gbọ́mọ Ogundstaste of Loveit's Her Dayọ̀bú Alvy A Man Mangroundlight Will Coceted Twin ríranton Késárìọba 66 With Lagos Love Àwọn Ami-eye Bíṣọ́ọ̀bù Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Samuel Adeṣùjọ Ademulegun jẹ́ ọ̀gá kan lábẹ́ ile-ise ologun ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni oga agba awon omo ogun ile ni odun 1966, ti o di de ipo ogagun pata fun awon omo agba.Ológun ni ile Naijiria.O gba ipo oga oga Corps nibi ise ologun ni odun 2, oun ati Aguiyi, amikari, Gaber ati baba Ogundi Ogundi Ogunepo Ogun- World lati o gba ko agba lati agba lati agba lati lati lati o ni ko ori ori naa ni awon omo agba ni ile agba ni omo ogun ni odun lati lati o di de iwe ko ni oun fun awon omo agba ni ile Yoruba ni ile ori ori agba lati o gba ise ologun, oun lati ami ami lati ami osere oorun ti o ni awon agba ni awon omo agba ni ile Naijiria, Mo gba ere Gise ni odun agba awon omo agba ati omo ni odun 1966, ti o di agba ori agba lati agba fun awon omo agba ni ile Naijiria ni ipo Naijiria. lati lati ilu ilu ologun ni odun Yoruba, oun ati irin ni ile kejila _*pata ati Baba agba ni ilu agba ni ile ni ilu agba ni ilu Ogun ni odun lati o ni o ni odun agba ni odun girama fun awon omo agba ti ile agba ni ipo agba ko agba girama ni ile ati lati odun ipo agba lati po sinu agba ilu G ni odun Ogun Ogun agba ni lati agba ori oun ni ilu agba*_
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ológun tí wọ́n ń díje sí ipò Goc, ẹ̀yin tí ẹni tó dipò náà mú tẹ́lẹ̀ fẹ̀yìn tì ní ọdún 1965..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ lẹ́yìn rẹ̀ níbi iṣẹ́ ológun ń fòmú nígbà tí wọ́n rí wípé ọ̀gá wọn ń ṣe àṣepọ̀ pẹ̀lú ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ahmadu Bello..
wikipedia
yo
Wọ́n pa òun àti ìyàwó rẹ̀ nínú Ìdìtẹ̀rängnäjọba ọdún 1966, nínú ìdìtẹ̀gbàjọba tí Timothy Owuatu léwájú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ni ni ibùdó ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́ni àwọn ológun ni ó já wọlé rẹ̀ tí ó sì yìnbọn lu òun àti ìyàwó rẹ̀lórí ibùsùn wọn.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Zaya Maimálà je okan lara awon omo ologun ile Naijiriati o de ipo Briga-General, ti won si oke seku pa a ninu 2..
wikipedia
yo
Oun ni adari pata pata fun iko ologun 2nd Brigade, ti ilu Apapa, ni Ipinle Eko ni ọdun 1966.ibẹrẹ aye rẹwọn bi Maimálàri ni Ipinle Yobe, o lo siílẹ̀-ẹkọ Brewa College, ni ilu Zaria..
wikipedia
yo
Oun ati ọrẹ igba ewe rẹ, lagbowan Umar dara pọ mo Royal West Africa Fronative Force ni ọdun 1950..
wikipedia
yo
Látàrí kíkó ọ̀pọ̀ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà sínú ipò ọ̀gá lẹ́nu isẹ́ ológu ilẹ̀ Nàìjíríà, ó lọ sílé èkó regular Officers Training School, tí ó wà ní Teshie Ghana àti The Royal Military Academy, Shurst..
wikipedia
yo
Òun àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ Wwan ni wọ́n jọ lọ sí Srosrt, ṣùgbọ́n wọ́n lè lwan ní tirẹ̀ kúrò lẹ́nu iṣẹ́ ológun..
wikipedia
yo
Lawan tun je okan lara awon ologun ti won koko fi sipo Officer Corps of the Nigerian Army..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ ní ibùdó Ìkẹ́kọ̀ọ́ àwọn Ológun àti adarí ikọ̀ ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ọmọṣẹ́ ológun ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọjọ́mà sàna tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ olùdarí Arts ti West Africa fún British Council..
wikipedia
yo
O n sise pelu ile-ise Adani ati ti ijoba ni UK ati West Africa lati pese awon ise lóríṣiríṣi fun idagbasoke.igbesi aye ati eto-ẹkọ iṣẹ́iṣẹ́ chemistry ni ojoma koko fe lo ka iwe iwe amo o pada se arts..
wikipedia
yo
O gboye Honours diploma Network ni niit Abuja Centre ni ọdun 2004.Ni ọdun 2008, o gba iwe-ẹri Certificate Project Management ni APm, UK..
wikipedia
yo
ó lọ sí Òọnn Institute of Arts Management, University of Maryland níbi tí ó ti gboyè Arts Management Fellowship Arts, Entertainment, àti Media Management ní ọdún 2015.Iṣẹ́ rẹ̀òun ni Arts and Administrative Assistant ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2006 wo 2007..
wikipedia
yo
O je adari connected Africa Arts Project ni Naijiria ni odun 2007 wo odun 2009..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, ó jẹ́ olùdarí Diversity, performance and Evaluation ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je oludari arts ni Naijiria lati odun 2010 wo 2017..
wikipedia
yo
Ó di olùdarí Arts ní West Africa Lọ́dún 2017.Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ tí ó gbani ọdún 2014, ó gba àmì-ẹ̀yẹ “10 Most powerful People, under 40” ní “Nigeria’s Arts and Culture", a sì tún yan - án fún "Young Person of the Year” fún "Future Awards Africa” ní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó gba àmì-ẹ̀yẹ "100 Most Influential Nigerians", ó sì tún gba àmì-ẹ̀yẹ "100 Most àìnípẹ̀kun Women in Nigeria" ní ọdún kan náà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
LateEfah Moyosore Durosinmi tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1957 jẹ́ olùkọ́ àgbà ti Chemistry àti Gíwá tó rí sí ọ̀rọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Obafemi Awolowo University, tí ó wà ní Ile-Ifẹ̀.Ìgbésí Ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ keje keje Oṣù Keje ọdún 1957 ni a bí Dr..
wikipedia
yo
Baba rẹ ni olóògbé Alhaji Tijani Akanni Williams, iya rẹ si ni WSamot Abeni kaká..
wikipedia
yo
Ile-iwe Patience Moderam girls' Private School ni Ipinle Eko ni o ti bẹrẹ eto ẹkọ rẹ..
wikipedia
yo
O si lọ si Girls' Secondary Grammar School ni Ipinle Eko ni odun 1974-1976..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1986, ó gboyè Master of Science (M.Sc.) nínú Anatical Chemistry ní Ifásitì kan náà..
wikipedia
yo
LateEfah jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ fọ́Mwan.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
isoken ògìemwọnyi tí í se ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ olùdarí The Obsidian way àti oníṣòwò tó da Zazai sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ó maa ń ran aṣọ ó sì tún maa ń ṣàfi àwòrán fún aṣọ lọ́lẹ̀ lórísítọ.Ẹ̀-ẹ̀kọ́-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ tó yàn làUniversity of Nottingham ní ògìem lọ tí ó sí gboyè (ll Law ìdálọ ìdá ìdáláẹ̀lé..
wikipedia
yo
O si tun ṣe Post Graduate Studies ni hospitality ati Masters degree ninu Management..
wikipedia
yo
Oiwewọnyi oludasile-keji ti WinterFell Ltd, ti o ni le Petit Marche Nigeria ati l' Pacemarks Trade..
wikipedia
yo
Ogunwọ̀nyí àti wọnúọlá ọdúnsì ló jẹ́ alágbàátẹ̀rù le Petit Marche (lpm)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó kópa nínú MTN Lagos Fashion & Design Week/British Council, orúkọ ìdánimọ̀ rẹ̀ fún ayẹyẹ náà ní Obsidian..
wikipedia
yo
Ó sì yege gẹ́gẹ́ bíi young creative Entrepreneur of the Year..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, ó kópa nínú Pitti Imine Trade Show ní ìlú Florence lórílẹ̀-èdè Italy.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Humuani Amoke Alaga, (1900 – 29 January 1993)ti gbogbo eniyan mọ si Mama Humuani Alaga jẹ ọmọ ilu Ibadan, ni ipinle Nigeria..
wikipedia
yo
Humani jẹ olùfilo ati olùtajà alainikankan ti o wa sinu iṣowo ọrọ..
wikipedia
yo
O ko awon alainitẹ awon obinrin ni odun 1938 lati beere fun iye owo ti o dọgba ati ipo ise ti o dara julo fun awon obinrin..
wikipedia
yo
O jẹ ikan ninu àwọn olùdásílẹ̀ ti Igbimọ Àwọn Àwùjọ Àwọn Obirin ti Ipinle ni ọdun 1959 ..
wikipedia
yo
O ku ni Oṣu Kini, Ọjọ mọkandi, ọdun 1993 ni Ibadan .ni ibẹrẹ aye a bi Humuani si ilu Ibadan ni ọdun 1900..
wikipedia
yo
Oruko baba re si je Alfa Alaga ti o je alufaa Musulumi ati olùṣòwò, Iya re si je Asìbáwí ladebo Alaga..
wikipedia
yo
Ó béèrè si ní ta ọ̀já aṣọ àti ìlẹ̀kẹ̀ ní ìgbà tí ó kéré gan..
wikipedia
yo
O ṣe igbeyawo ni igba ti o pe ọmọ ọdun mejidinlogun.Iṣẹ Humuani bẹrẹ owo rẹ nipa tita aṣọ, leyin igbeyawo rẹ ni ọdun 1925..
wikipedia
yo
Lẹhinna o ṣii itaja kan laarin 1928 ati 1929 o si di oniṣowo fun awọn ile-iṣẹ miiran..
wikipedia
yo
O di adari awọn ti wọn ta aṣọ ni ọdun 1934 ni ọja gbàgì ni ilu Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O wa laarin awon oludasile ẹgbẹ Ifelodun ni ọdun 1930..
wikipedia
yo
ní ọdún 1958, lẹ́hìn ìgbàtí wọn kò gba ọmọ rẹ̀ obirin si ile-iwe Kristiani, òun pẹ̀lú àwọn obìnrin mọ́kànlá mìíràn dá àwùjọ kan tí ó gba orúkọ Isabatudeen Society (WA)) lati ṣẹda ile-iwe alakoko kan fun awọn ọmọbirin..
wikipedia
yo
O da ipilẹ ile-ẹkọ giga ọmọbirin Isabatudeen.ijagbara awọn obinrin iṣowo aṣọ ni ọdun 1938 ṣe atako si awọn oniṣowo ara ilu Lebanoni ti n ṣe bi Alagbọràn ninu Iṣowo Aṣọ..
wikipedia
yo
humani se atako si awọn oniṣowo ara ilu Lẹ́baon to ta ọja ni aarin awọn ibi ti o ye ki awon yoja ibile wa..
wikipedia
yo
Nipa atako yi ni o pada yori si ṣiṣẹda National Council of Women's Societies (NCWW) ni ọdun 1959..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1953, ó darí ẹgbẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣọ ti ìlú Ìbàdàn sí ìgbógunti lòdì sí gbígbé Ọjà dùgbẹ̀ lọ sí ibi titun..
wikipedia
yo
Àwọn alátakò lọ sí àfin ọba láì wọ bàtà, wọ́n sì sọ fún ọba pé kò gbọdọ̀ gbé ọjà nã kúrò..
wikipedia
yo
Ó tún mú àwọn obìnrin ọjà lọ sí ààyè gómìnà láti fi ẹ̀hónú hàn ní pípa nípa bí àwọn ológun ṣe pa àwọn alátakò ní ọdún 1978..
wikipedia
yo
O tun ṣe iṣeduro fun owo dọgba fun okunrin ati obinrin nigba ibewo re si Gomina Ipinle.Awon itọkasi awon ara Naijiria..
wikipedia
yo
Willie Obiano (Ọjọ́ìbí August 8, 1955) je oloselu, onile-si ati àṣIjoba ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ohun ni Gomina Ipinle Anambra lọwọlọwọ lati ọdun 2014.itọkasiàwọn gomina ìpínlẹ̀ Anambra..
wikipedia
yo
Adegboyega Oyetola (ojoibi September 29, 1954) jẹ́ olóṣèlú ará Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Osun.Ìtọ́kasí gómìnà ìpínlẹ̀ Osun..
wikipedia
yo
Damilola anwò-Adé tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ Olùṣàkóso ìyẹ́a digital development limited tí ó ń bá ṣiṣẹ́ pọ̀..
wikipedia
yo
Oun si ni oludasile Code.eto-ẹkọ ati iṣe rẹBabcock University ni Damilola lo ti o si kẹkọọ nipa Information Resources Management ni ọdun 2003 wọ ọdun 2007..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀ síwájú láti gba oyè master's degree nínú education planning and international development ní the Institute of education, u ní ìlú London lọ́dún 2012..
wikipedia
yo
Damilola ni Olùṣàkóso ìyẹ́ Digital Development Limited tí ó ń bá ṣiṣẹ́ pọ̀..
wikipedia
yo
Abneri jẹ́ ọ̀kan lára àwọn irinṣẹ́ ayélujára tó máa ń pèsè ojútùú fún àwọn ilé-iṣẹ́ àti ọwọ́ lóríṣiríṣi.Bákan náà, Code jẹ́ ọ̀kan lára àwọn irinṣẹ́ ayélujára tó máa ń pèsè àyè sílẹ̀ fún àwọn ọmọdé (ọmọ ọdún márùn-ún sí méjìdínlógún) láti nímọ̀ lórí àwọn irinṣẹ́ ayélujára..
wikipedia
yo
Ó maa ń yọọ́ iṣẹ́ lórísísí tó dá lórí ayelujara lati mú lo ipele tó kan..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ ICT lórísilórí níbi tó ti n kọ́ àwọn èèyàn ní Intel àti un Women Nigeria..
wikipedia
yo
Department of State’s Bureau of Educational and Cultural Affairs Yan-an gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ṣísili Valley lọ́dún 2017.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọmọbọlá Olubusola Johnson (Bii ni ojo kejidinlogbon osu kefa odun 1967) je omo orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìkan nínú àwọn Oni ìmọ̀ tẹgology, òun pẹ̀lú sì ni alága ẹgbẹ́ Alliance for AFforDA Internet (A4A)..
wikipedia
yo
O jẹ too iṣoro tẹkin tẹlẹ ni abẹ́ akoso olori orilẹ ede Goodluck Jonathan..
wikipedia
yo
.Ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó ka ìwé ní ilé-ẹ̀kọ́ International School Ìbàdàn, ó sì ṣe ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ ní University of Manchester nínú gbinÓlo and Elerẹ̀ Engineering..
wikipedia
yo
O lo se Masters degree re ni King's College ni ilu London..
wikipedia
yo
Ó gba Doctorate degree rẹ̀ ní Cranfield University nínu Business Administration.Iṣẹ́ OmoBola jẹ́ olùdarí fún ilé iṣẹ́ ACCenture ní Nàìjíríà kí ó tó di Mínísítà iṣoro tẹology..
wikipedia
yo
Ó dáwá sí ní ṣíṣe fún ACCenture ní ọdún 1985 ní ìgbà tí ilé-iṣẹ́ náà sì ń jẹ́ Andersen Buman..
wikipedia
yo
OmoBola je adari ero ibanisoro tẹkinology eyi ti won da sile lati se iyipada ni ijoba Nijiria..
wikipedia
yo
OmoBola wa ninu awon to da egbe obirin wimbiz ni odun 2001..
wikipedia
yo
O ti gba ọpọlọpọ ìyìn lati ọ̀dọ̀ àwọn ará ìlú lati ìgbà tí o ti di òjíṣẹ́ ìjọba ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
Ìkan nínú àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ní ìfilọ́lẹ̀ tí nígcom-irra Satellite..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ó wà ní ipò òjíṣẹ́, ẹẹdẹgbẹrin èrò kọ̀mpútà ni ó fi ranṣẹ sí àwọn ilé ẹ̀kọ́ ní inú ètò tí ó pè ní school access Programme (Sap).
wikipedia
yo
Ni ọdun 2013, ni osu karun, OmoBola fun olori orile ede Goodluck Jonathan ni eto National Broadband Plan fun odun 2013 de odun 2018.Ni osu kesan odun 2013, orile ede fi OmoBola si ipo adari fun ise awon ojise imo ijinle ati tẹ:“ology ti orile ede apapoawon itọka síàwọn ara Naijiria..
wikipedia
yo
Marion Walter Jacobs (May 1, 1930 – February 15, 1968), to gbajúmọ̀ bí i Little Walter, jẹ́ olórin, akọrin, àti akọ̀wé-orin Blurs..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ara ilẹ̀l America tí ó kọrin lọ́nà tuntun bi i Jimi Henedx..
wikipedia
yo
Iṣowokorin rẹ mu ki ọpọlọpọ eniyan ni ìrètí ohun ti orin Blu maa da lọjọ iwaju.Awon itọkasiàwọn olorin ara Amerika..
wikipedia
yo
BERBERRY Gdy III (known Professionally as BERBERRY GUR Jr., Born November 28, 1929) jẹ́ ọ̀gá ilé-iṣẹ́ olóòtú, olóòtú àwo-orin, akọ̀wé-orin, olóòtú fíú àti olóòtú ètò láti ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ohun ni oludasile ile-iṣẹ nigbati mọ́tọ̀wn ati awọn apa rẹ̀.Ìtọ́kasíàwọn olorin ara Amẹrika..
wikipedia
yo
Òdòdó, tí a mọ̀ nígbà míràn bí ìtànná ewéko, ní èyí tó ní ibi àtúnbí nínú àwọn ọ̀gbìn olódodo (àwọn ọ̀gbìn tí a mọ̀ sí Magnolioìdánita, tàbí angiosperms)..
wikipedia
yo