cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ruth Kadiri jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùkọ́ fọ̀ràn àwoka eré ìtàgé àti olùgbéré jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọ́n bí Ruth ní ọjọ́ Kẹ́tàlélógún oṣù kẹta ọdún 1988 ní ìlú Benin tí ó jẹ́ olú-ìlú fún ìpínlẹ̀ Ẹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Yábàá, tí ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Business Administration, bákan náà ni ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde gboyè àkọ́kọ́ ní Yunifásítì ìlú Èkó nínú ìmọ̀ ibà ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (Mass Communications) .Àwọn ìtọ́ka sí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
mìírànber Omoseni (seni) Sulyman (bi ni ọdun 1985) jẹ otaja orilẹ-ede Naijiria kan ati Igbakeji Alakoso, ni AnDela, Imọ-ẹrọ Agbaye bi iṣẹ Iṣowo.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ ni oludari awọn iṣẹ fun AnDela ni Nigeria ati lẹhinna di alakoso orilẹ-ede ti Ilu mẹfa ni oṣu mẹfa lẹhin naa .. | wikipedia | yo |
Sulyman tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Igbimọ Awọn oludari ni Fate Foundation.Awon itọkasiawọn oniṣowo ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
je ajo ti awon onisowo ati ile-ise aládàáni da sile lati ṣẹ̀gbé fun ÌGBÓGUN ti ajakale arun ẹran korona lórílẹ̀-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Àwọn Parakoyi oniṣowo bíi Aliko Dangote, Femi Otedola, opo awon olówó miiran ati awon ile-iṣẹ nla-nla ni won gbìmọ̀pọ̀ da ajo yii sile lati se ìkówójọ fun ajo ijoba apapo, ti o n se kòkárí fun igbogun ti ajakale arun coronavirus, Nigeria Centre for Disease Control, NCDC.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dá ìlékanCOVID sílẹ̀ lọ́dún 2020 ní Nàìjíríà lọ́wọ́lọ́wọ́, ẹgbẹlẹmùkù owó ni wọ́n ti kó jọ láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìjọba-àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti gbógun ti ìjíkalẹ̀ àrùn Coronaxide Ìtọ́kasíCOVID-19.. | wikipedia | yo |
Nínú ìmọ̀ ẹ̀yà ara ènìyàn, ẹnu ni ẹ̀yà ara àkọ́kọ́ tí ó kángun sí ọ̀nà ọ̀fun ti ohun jíjẹ àti ohun mímu ń gbà kọjá, tí ó sì pèsè itọ́ fún ìrọ̀rùn ahọ́n kí ọ̀rọ̀ ó lè já geere.. | wikipedia | yo |
gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara ìfọ̀, ẹnu ní agbára láti pèsè àti láti gbá itọ́ dúró pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Epithelium tí ó wà nínú ẹnu.Lára iṣẹ́ rẹ̀, láti ẹnu ni iṣẹ́ dídá oúnjẹ ti bẹ̀rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀, ó tún ń ṣiṣẹ́ ìfọ̀, ọ̀rọ̀ sísọ tàbí ìbánisọ̀rọ̀nígbà tí àkọ́ṣe iṣẹ́ ọ̀hún ń ti inú taàná ahọ́n , ètè àti árugbọ̀n nílò oríṣiríṣi ohùn àti ọ̀rọ̀.ìpínsísọ̀rí ẹnua lè pín ẹnu sí oríṣi ọ̀nà méjì, àkókò ní àbáwọlé ẹnu tí wọ́n ń pè ní (fẹ́sìti. àti ọ̀fun.Ìrísí rẹ̀ sábà ma ń yọ̀ tàbí tútù nígbà gbogbo pẹ̀lú omi ẹnu tí a mọ̀ sí itọ́.. | wikipedia | yo |
Inú ẹnu ni ẹ̀yin ń gbé nígbà tí ẹ̀tẹ̀ sì jẹ́ ìlẹ̀kùn àbáwọlé sí ẹnu àti gbogbo ẹ̀yà ara inú tó kú pátá.Àwọn ìtọ́ka síẹ̀yà ara.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀yà ara ìfọ̀, tàbí ìbúsọ́rọ̀, ni àwọn ẹ̀yà ara kan tí ó dá wà fún ọ̀rọ̀ sísọ tàbí kí a lò wọ́n fún àgbékalẹ̀ èdè láti ẹnu.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀yin gbọdọ̀ wà ní mímọ́ láìsí jíjẹrà, kí ó funfun kí ó le koko kí ó sìn má dán pẹ̀lú orí ti mú dáradára.. | wikipedia | yo |
Àgbàlagbà yẹ kíó ní ẹ̀yin méjìlélọ́gbọ̀n (mẹ́rìndínlógún ní abala òkè àti ìsàlẹ̀).. | wikipedia | yo |
Ni ọdún meji ati àbọ̀, ọmọdé yẹ ki ó ni ẹyin ogun kéékẹ̀, (mẹwa-mẹwa ni abala oke ati ìsàlẹ̀) iwadi fi idi rẹ múlẹ̀ pé àwọn ohun ti kò tọ́ nípa ẹ̀yin ni, ẹ̀yin ti kọ pé, ẹ̀yin ti ó sọnù, ẹ̀yin ti ó gé ati ẹ̀yin ti kò dúró déédé.. | wikipedia | yo |
Àwọn Aran tí ó Ma ún ṣe ẹyìn ní wọ̀nyí jíjẹrà nípa ìgò oúnjẹ ọmọdé (baby-bottle tooth ?’y), lólólis, meth mouth and íṣe's teeth.èrìgì òkèèrìgì tìsàlẹ̀,àjà ẹnu,kàá ọ̀fun,ta àti ahọ́n pẹ̀lú ìṣesí rẹ̀.Àwọn ìṣesí ẹ̀yà ara ìfọ̀ìṣesí méjì ló wà fún àwọn ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó wà, ìṣesí Alkòókò ní ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó ń sùn.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀tẹ̀ ni ẹ̀yà ara ti ó jẹ́ àbáwọlé sí ẹnu ọmọnìyàn ati ẹranko ti fara hàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó mú kí orí ó pẹ́ níye.Ètè tún jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó má ń lọ sókè, sílẹ̀, sọ́tùn ún ati òṣì Yals nígbà tí a bá ń jẹun, mumi, tabi tabi sọ̀rọ̀.Àwọn ìtọ́ka síẹ̀yà ara ìfọ̀.. | wikipedia | yo |
Ahọ́n jẹ́ ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó jẹ́ iṣan tí ó wà ní inú ẹnu ènìyàn tàbí ẹranko tí ó jẹ́ eléégún lẹ́yìn.Iṣẹ́ tí ahọ́n ń ṣeahọ́n ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara ti ọmọ ènìyàn ń lò fún ìbánisọ̀rọ̀, jíjẹ oúnjẹ, tí gbogbo ẹranko tókù sì ń lò ní ìlànà kan náà, yàtọ̀ sí ìbásísọ̀rọ̀ bí ti ọmọnìyàn.. | wikipedia | yo |
Ahọ́n wúlò púpọ̀ fún jíjẹ àti dídá oúnjẹ nínú àgọ́ ara nítorí àwọn èròjà àmù oúnjẹ dá tí wọ́n ń pè ní (enzyme).. | wikipedia | yo |
Lára ahọ́n náà ni ìtọ́wò ti a fi ń mọ adùn àti kíkan.. | wikipedia | yo |
Ahọ́n tún sábà ma ń tutù látàrí èròjà tí ó ń pèsè ìtọ̀ tí ó wà lára rẹ̀.. | wikipedia | yo |
ahọ́n tún ma ń ṣe ìmọ̀ tótó ẹnu nígbà gbogbo, paá pàá jùlọ ẹ̀yin.. | wikipedia | yo |
kókó iṣẹ́ ahọ́n nì kí ó ṣètò ìró ohùn di ọ̀rọ̀ lára ènìyàn àti ohùn lásán lára àwọn ẹranko tókù.Ọ̀nà tí ahọ́n pín síahọ́n ọmọnìyàn pín sí ọ̀nà méjì, àkókò niìpín ibúsọ̀rọ̀, èyí wà ní ọwọ́ iwájú nígbà tíìpín kejì jẹ́ taàná tí ó wa lọ ẹ̀yìn mọ́ ọ̀nà òfin.. | wikipedia | yo |
Apá ọ̀tún àti apá òsì ni iṣan ti ó nà tẹ̀ẹ̀rẹ̀ tí ó ń gbé ẹ̀jẹ̀ kiri gbogbo ara ahọ́n náà.Àwọn ìtọ́ka sí ẹ̀yà ara ìfọ̀.. | wikipedia | yo |
Itọ́ ni omi ara tí ó ń sun láti ibùsùn kan nínú ẹnu yálà lára ènìyàn tàbí ẹranko.. | wikipedia | yo |
Lára ènìyàn, itọ́ tí ó ń sun tó ìdá 99.5 Omi pẹ̀lú (Electrolytes), kẹ̀lẹ̀bẹ̀, ẹ̀jẹ̀ funfun, Epitheli cells níbi tí DNA ti ma ń sun jáde.Iṣẹ́ tí itọ́ ń ṣẹ́itọ́ ma ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí bomirin ẹnu, rinrin oúnjẹ ó sì tún ma ń ṣiṣẹ́ ìgbẹ̀mí, tí ó sì tún ń ìrọ̀rùn igbe ọ̀rọ̀ jáde kí ẹnu ó má ba gbẹ.Àwọn ìtọ́ka síomi ara.. | wikipedia | yo |
Stephanie Dorgbáà Mills (ojoibi March 22, 1957) jẹ́ akọrin, akọ́rọ́-orin àti òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Mills gbajúmọ̀ nígbà tó kópa nínú eré orítage the wíZ gẹ́gẹ́ bi “Dorothy” láti ọdún 1975 títí dé 1977.. | wikipedia | yo |
Orin rẹ̀, "Home" láti inú eré na di onípò Kínní ní Amẹrika fun Chart R&B ati ikan ninu awọn orin rẹ to gbajumọ julọ.. | wikipedia | yo |
Mills gba ẹ̀bùn Grammy fún akọrin obìnrin R&B didarajulo fun orin re "Never knew Love Like This Before" ní ọdún 1981.Ìtọ́kasíàwọn akọrin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Emily "Sysy" Houston (Orúkọ ìdílé Ẹnirouï; Ọjọ́ìbí September 30, 1933) jẹ́ akọrin Soul àti Gospel ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Houston ni Mama akọrin Whitney Houston, Iya-iya fun Bobbí Kristina Brown, Aunti fún àwọn akọrin Dinne àti dèé D Warwick, àti ìbátan akọrin opera Leonne Price.Ìtọ́kasí akọrin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Aliko Dangote Gcon (Ọjọ́ìbí 10 April 1957) je onisowo ati Olore ara Naijiria to oludasile ati Alaga ile-ise Dangote Group, ile-ise aloero gbangba ni Afrika.. | wikipedia | yo |
Gbogbo ohun ini rẹ to US$8.1 billion (March 2020), ni January 2020, ohun ni eni bakan 88k ni agbaye ati eni oloro julọ ni ilẹ Afrika.Ni osu Kọkànlá odun 2021, Sani Dangote, Igbakeji Alakoso (vp) ti egbe Dangote ati aburo Aliko Dangote, Kuitọkasiitọkasiàwọn oniṣowo ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Èyí ma ń mú ìdíwọ́ wà nínú ìgbésẹ̀ ìbára-ẹni ṣòro, tí kìí sì jẹ́ kí a gbọ́ ara ẹni ẹ bí a bá ń sọ̀rọ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Edgar Chagwá Lundagu (ọjọ́ìbí 11 November 1956) jẹ́ olóṣèlú àti ohun ní Ààrẹ ilẹ̀ Sámbíà lọ́wọ́lọ́wọ́ láti January 2015.. | wikipedia | yo |
Lábẹ́ ààrẹ Michael ṣátá, Lunda ló jẹ́ alákọ́so fún ìdájọ́ àti àpapọ̀ fún ẹ̀tọ́ àbò.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ikú òjijì Ààrẹ ṣátá ní October 2014, Lunda jẹ́ gbígbà bí ẹnialedi fún ẹgbẹ́ òṣèlú Pattẹ́nì Patgle Front.. | wikipedia | yo |
O padanu idibo alakoso 2021 si alatako igba pipe hakamọ́ni hiChilema.Awon itọkasiawon Aare ile sambíà.. | wikipedia | yo |
àbbá Kyarí (23 September 1952 – 17 April 2020) jẹ́ olóṣèlú ará Nàìjíríà tó ṣiṣẹ́ bí ọ̀gá àwọn òṣìṣẹ́ fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà láti August 2015 di April 2020.Ìtọ́kasí àwọn olósèlú ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
agogo jẹ́ ohun èlò tí à ń lò láti sodíwọ̀n iye wakati ti wà ninu ọjọ́ kan ṣoṣo, and indicate time.Agogo jẹ́ ọ̀kan pataki ninu ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ tí ọmọnìyàn ṣe àwárí rẹ̀ láyé.. | wikipedia | yo |
O jẹ okan lara ohun ti a fi n se ònkà ọjọ, osu ati odun.Ninu imo nipa aago, ohun ti won gba wipe agogo ni aago ti o ba dun gbágaun, nigba ti won pe eyi ti kii dun ni kàjọ. | wikipedia | yo |
Láyé òde òní, agogo ni ohun tí a mọ tí ó ń ṣàfihàn ònkà ọjọ́.. | wikipedia | yo |
agogo lè jẹ́ èyí tí a fi kọ́ sí ara ògiri ilílé tàbí èyí tí a so mọ́ ọrùn ọwọ́ wa láti lè má fi mọ òǹkà àti àsìkò inú òjò.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
, NCDC (Gbọ̀ngàn Nàìjíríà fún ìjanu ÀRÙN) jẹ́ olórí Àjọ Ètò Ìlera Ìjọba Àpapọ̀ tí ó ń bójú tó ètò àjàkálẹ̀ Ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àjọ yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso ilé-iṣẹ́ ètò ìlera ìjọba àpapọ̀, Federal Ministry of Health (Nigeria) ti Olú ilé Iṣẹ́ Àjọ náà sin wa ní Abuja, Nigeria.. | wikipedia | yo |
Ọ̀gbẹ́ni Chikwe Ihekwe ni olórí Àjọ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ .Pàtàkì Iṣẹ́ Àjọ yìí ní láti dá ààbó bo Ìlera gbogbo ará ìlú àti láti dẹ́kun ìlera àwọn ènìyàn nípa ìdarí àti ìdènà àwọn àjàkálẹ̀ àrùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àjọ yìí tún wà fún ṣíṣe kòkárí bí àrùnkárùn kò ṣe ní gbinàyá, nípa ṣíṣe àkójọ pọ̀ ìròyìn nípa àrùn kan, ṣé àgbẹnu ipa irú àrùn bẹ́ẹ̀ láti dènà ríràn ká wọn láwùjọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Osuola Abimbola Richard AkinJide,[ Agba agba ti orilẹ-ede Naijiria] ti a bi ni ojo kerin, osu Kọkànlá odun 1930, ti o si ku ni ojo kọkànlé-logun osu kerin, odun 2020(4 November 1930 – 21 April 2020)o je omo bibi orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
, ó jẹ́ ògbóǹtarìgì agbẹjọ́rò àgbà, olóṣèlú takuntakun àti oníṣòwò nlá ní í ṣe.. | wikipedia | yo |
O ti fi igba kan je Minisita fun eto Eko ni akoko isejoba Àwaawarawa ekeji leyin ijoba ologun ni orile-ede Naijiria, bakannaa ni o si je alákòóso idajo labe ijoba Aare Shehu Shagari.Awon itọkasiawon agbejoro agba ile Naijiri oloselu ara Naijirimeje omo Ibadan.. | wikipedia | yo |
Odun igogo jẹ́ ọdún ìbílẹ̀ Yorùbá tí ó ma ń wáyé ni ìlú owó ìpínlẹ̀ Oǹdó ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ma ń ṣe ọdún yí ní gbogbo oṣù kẹsán an sí oṣù kẹwàá ní ọdọọdún ní ibú ọlá fún olórí oronsen tí ó jẹ́ olórí ọba rereńgésokùdùkù ọdún yí, Ọba tí ó bá wà lórí ìpò àti àwọn Olóyè láàfin ọ̀ra.Múra bí àwọn obìnrin pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n fi ìlẹ̀kẹ̀ gigi ṣe lọ́lẹ̀, tí wọ́n máa sí dirun gẹ́gẹ́ bí àwọn obìnrin tí ma ń ṣe | wikipedia | yo |
Wọ́n yóò dé fìlà, tí wọn yóò sì ma lu ìlù pẹ̀lú àwọn orin ọlọ́kan ò jọ̀kan, tí wọn yóò sì ma yin ìbọn sókè lásìkò ọdún náà.Ìtàn bí ọdún náà ṣe bẹ̀rẹ̀ọdún ìgògó bèrè ní nkan bí ọgọ́rùn ún mẹ́fà ọdún sẹ́yìn ni ọba Olówó Àyérunẹní fẹ́ olórí ọ̀rọ̀sen tí ó jẹ́ arẹwà àti ọlọ́rọ̀ tí ọba náà kò mọ̀ wípé òrìṣà ni.. | wikipedia | yo |
Olori yi fi gbogbo nkan ke olówó yi kódà to fi mọ́ agbara, ti ọba naa si nifẹ rẹ tọkab tọkàn.. | wikipedia | yo |
olóri ọrọ̀ṣẹ̀ ni àwọn èwo kan tí kìí fẹ́ kí àwọn ènìyàn ó ṣe nítòsí rẹ̀ tàbí kí ó fojú rí.. | wikipedia | yo |
Fúndí èyí, ọba rereńgé kó fún àwọn olórí tó kù kí wọ́n má ṣe ṣe àwọn nkan wọ̀nyí.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kan, olórí Orosen ní gbólóhùn aṣọ pẹ̀lú àwọn olórí tó kú nínú àyán.. | wikipedia | yo |
Àwọn olórí wọ̀nyí wá gbìmọ̀ pọ̀ tí wọ́n sì ṣe gbogbo nkan èwo tí kò fẹ́ràn sílẹ̀ fún nígbà tí kò sí nílé.. | wikipedia | yo |
Awon iwa ọ̀dàlẹ̀ ti awon olori tókù hu yi ni o mu orosen binu kuro ni Afin fun won.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó ń bínú kúrò ní àfin lọ́jọ́ náà lọ́hùn ún, àwọn ìlàrí ọba àti àwọn ìjòyè gbìyànjú láti dá dúró kí ó má lọ ṣùgbọ́n agbára wọn kò káà.. | wikipedia | yo |
Ó sáré títí ó dé ibìkan tí wọ́n pè ní “Ùgbò lájà", níbi tí ó sinmi sí.. | wikipedia | yo |
Ibi ni àwọn Àkọ́dá ọba àti àwọn ìjòyè ti gbìyànjú láti mú padà wá sí àfin.. | wikipedia | yo |
Akitiyan àwọn ènìyàn wọ̀nyí túbọ̀ bí olórí ọrọsen nínú tí ó sì bínú pòórá wọgbó “Igbó OLUWA”Lọ láì mú ìgbànú tabi ọjà rẹ̀ kí ó tó wọgbó, tí wọ́n sì dá ọjà náà padà fún ọba Ìyéku láàfin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sọ igbó Olúwa'' di ojúbọ olórí yí tí wọ́n sì ṣe ère rẹ̀ lọ́jọ̀ sí “Ùgbò lájà” fún ìrántí rẹ̀ wípé kò sí ohun tó lè mú olórí náà padà wá sí ìlú mọ́.. | wikipedia | yo |
Ọjọ́ àwọn ọmọdé jẹ́ ọjọ́ tí a yà sọ́tọ̀ lọ́dọọdún láti ṣe àjọyọ̀ ẹ̀yẹ fún àwọn ọmọdé lágbàyé.. | wikipedia | yo |
Ọjọ na yato lati orilede si orile-ede.Ni odun 1925, ojo awon omode kaakiriaye (International Children's Day) koko je yiyasile ni ilu Geneva nigba ipade agbaye fun itoju omode (World Conference on Child Welfare lati igbana, won ti nOṣù ni June 1 ni awon orile-ede pupo.. | wikipedia | yo |
Àjọ UN Unṣàjọ̀dún ọjọ́ àwọn ọmọde ní November 20.Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Nigbati akọ eniyan ba dagba, wọn kejiati ni okunrin.Ìtọ́kasí ọmọdeawon okunrin.. | wikipedia | yo |
Ìwé eré onítàn Aròkúta of God , ni wón gbé jáde ti odún 1964, ní ó jẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ tí gbajú-gbìs òǹkọ̀wé Chinua Achebe.. | wikipedia | yo |
Iwe yi ati things fall Apart pẹlu no longer at ease, ni wọ́n sọ wípé wọ́n jẹ́ ìwé eré oníṣe onítàn ti ìlapa-èrò wọn dọ́gba jùlọ, ti Èkó,Ibùdó Ìtàn, àti Olú-kókó ọ̀rọ̀ inú wọn náà sì fara jọra, tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pè nítrilogy.. | wikipedia | yo |
Ìwé yí dá lórí olú ẹ̀dá ìtàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Ezeu", tí ó jẹ́ baba aláwọ̀ fún abúlé àwọn Igbo tí ó pọ̀ ní àsìkò ìmúnisìn àwọn Gẹ̀ẹ́sì tí ó kojú ìtèmérè àwọn amúnisìn àti àwọn olùpọlọ ẹ̀sìn Kírísítì ní àsìkò ọdún 1920.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gbé ìwé náà jáde látàrí ipá ribi ribi ti Ilé Is Ìtẹ̀wé Heinemann African Writers series kọ ki ó le ṣeeṣe.oruko ti won pe iwe yi Ardi of God ni won fàyọ lati inú òwe àwọn ẹ̀yà Ìgbò ti o tumọ si 'ise Oluwa Awa Maridìí | wikipedia | yo |
Ìwé eré onítàn eléré oníṣe Arìdí of God gba àmì-ẹ̀yẹ ìdákojú tí jọck Campbell àti New Statesman Alákòókò irú rẹ̀ fún ìkọ̀wé ilẹ̀ Aduitan inú ìwé náà Léléìwé Egbatẹnirò Filẹ̀ Fse yí ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ nínú àwọn abúlé àwọn ẹ̀yà Ìgbò tí ó jẹ́ ìkan lára ìletò àwọn Gẹ̀ẹ́sì amísìn ní àsìkò ọdún 1920s.. | wikipedia | yo |
Ezeu jẹ́ baba Abọrẹ̀ òrìṣà Uulu tí ó kalẹ̀ sí abúlé Aluṣi, tí oríṣi ìlú tí àpapọ̀ orúkọ wọn ń jẹ́ Umuarọ n sìn.. | wikipedia | yo |
Ija kan bẹ silẹ laarin ilu Umua ati Okperí ti o je ilu kan nitosi Ukokoaro, ija yi wá sópin nigba ti ogbeni T.K WinterBottom ti o je asoju awon geesi amunisin ba won da si.Awon itọka si.. | wikipedia | yo |
Ìbọn jẹ́ ohun èlò ogun tí ẹnìkan lè mú tàbí gbé dání lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo.. | wikipedia | yo |
ó lè ṣeé lọ dára dára, wọ́n ma ń gbé ìbọn dání pẹ̀lú ọwọ́ méjẽjì, tí wọ́n yóò sì fi ìdí rẹ̀ ti èjìká kí ó má bá jábọ́ lásìkò tí wọ́n bá ń yìn ín lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Awon eyi ti o je ibon osere tabi ibon ilewo kii nilo lati fi owo mejeji mu ki o to sise.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Àwọn ẹ̀yà Ìgbò ( , also ; tí wọ́n tún ń pè nìyíbá tàbí Heebo;tí àpèjẹ wọn ń jẹ́ ) ni wọ́n jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní àrin gbùngbùn ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Kò sí ẹni tó mọ pàtó ibi tí àwọn ẹ̀yà yí ti wà ṣaájú kí wọ́n tó já jọ sí ìletò tí wọ́n wà loni.. | wikipedia | yo |
Ilẹ̀ igbó pín sí ọ̀nà méjì, àkókò èyí tí ó wà ní apá àríwá tí ó wà ní apá odò ọya tó jẹ́ èyí tó tóbi ju ti ẹ̀ẹ̀kejì apá ìlà oòrùn.. | wikipedia | yo |
Àwọn ẹ̀yà ìgbà igbó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà tí ó pọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ adúláwọ̀.Àgbékalẹ̀ èdè wọnèdè Àwọn igbó náà tún jẹ mọ́ ẹbí Niger-Congo language Family.. | wikipedia | yo |
Èdè wọn pin si Orissarisi ẹka ede.The igbó Homeland Straddles the Lower Niger River, East and South of the Edoid and Iidd groups, and West of the Ibidòràn (Cross River) Cluster.Iṣẹ́ wọnohun tí wọ́n mọ àwọn ẹ̀yà yí mọ́ ni iṣẹ́ ọnà, iṣẹ́ àgbẹ̀ àti iṣẹ́ ọwọ́ ṣíṣe.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí wọ́n sábà ma ń gbìn jù ni iṣu, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ma ń gbin ẹ̀gẹ́ àti Taro.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Ni ojo ketadinlogbon osu keji odun 2020 ni ajakale arun COVID-19 fidi sole si orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Èyí wáyé látipasẹ̀ arákùnrin Italy kan tí ó padà sí Nàìjíríà pẹ̀lú ọkọ̀ òfúrufú ní ọjọ́ Kẹẹ̀ta Oṣù Kejì ọdún 2020.Bí àrùn náà ṣe tànkálẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta, Ìpínlẹ̀ Èkó fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ kejì múlẹ̀ látara ọ̀dọ́mọbìnrin kan tí ń ṣe ọmọ ọgbọ̀n ọdún tí ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tó sẹ̀sẹ̀ padà dé láti ilẹ̀ aláwọ̀funfun ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta.Ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta, Ìpínlẹ̀ Èkó tún ṣàwárí ìsẹ̀lẹ̀ tuntun mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kọkàn oṣù kẹta, a tún rí ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun mẹ́rin lórí àrùn COVID-19 ní Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ kan náà ni a gbọ́ pé arákùnrin tó mú àjàkálẹ̀ àrùn náà wọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti gba òmìnira lọ́wọ́ àjàkálẹ̀ àrùn náà.. | wikipedia | yo |
Eyi si ja si aṣeyọri akoko ti Ipinle Eko ni lori arun naa.Ni ojo kokanlelogun osu keta, ipinle Eko tun ṣawari iṣẹlẹ meje miiran.Ni ojo kejilelogun Oṣu Kẹta, iṣẹlẹ mẹfa miiran ni ipinlẹ Eko tun ṣawari.Ni ojo ketalelogun osu kẹta, ipinle Eko tun ṣawari iṣẹlẹ mẹfa.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sí tún fidi eni akoko ti o je alaisi latipase arun COVID-19 mule, eni ti o je àgbàlagbà omo odun mẹ́tàdínláàádọ́rin ti oruko re n je Suleman Achimugu, onimo ero ati oga agba tele fun ile ise pipeline and Product marketing, eniti o sese de lati ilu alawofunfun pelu ailera ara.Ni ojo kẹrinlelogun osu keta, ipinle Eko ṣawari isele kan.Ni ojo laarin osu keta, ipinle Eko ṣawari isele meta miiran.Ni ojo kerindinlogbon osu keta, ipinle Eko ṣawari isele mejila tuntun.. | wikipedia | yo |
.Ní ọjọ́ kẹtadinlọgbọn oṣù kẹta, ìpínlẹ̀ Èkó rí ìṣẹ̀lẹ̀ mẹjọ mìíràn.Lọ́jọ́ kan náà ni gomina ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu ṣe Ìkéde lórí àwọn ìjọba ìbílẹ̀ Èkó tí ó ní iye ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó pọ̀ jù lọ.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ kan náà ni wọ́n ṣe ìkéde pé èèyàn mọ́kànlá lára àwọn tí ó kó àrùn náà ni ó ti bó tí ó sì ti ní ìwòsàn pípé.Ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó rí ìṣẹ̀lẹ̀ mọ́kànlá mìíràn.. | wikipedia | yo |
Ni ojo karun-un osu kerin, ipinle Eko ri isele mokanla miiran.Ni ojo keje osu kerin, ipinle Eko ri isele mewaa miiran.Ni ojo kejo osu kerin, ipinle Eko ri isele mẹ́ẹ̀ẹ́dogún miiran.Ni ojo kesan-an osu kerin, ipinle Eko ri isele metala miiran.Ni ojo kewa osu kerin, ipinle Eko ri isele mejo mìíràn.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kokanla osu kerin, ipinle Eko ri isele mokanla mìíràn.Ni ojo kejila osu kerin, ipinle Eko ri isele meji miiran.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó rí ìṣẹ̀lẹ̀ mẹtala mìíràn.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹrinla oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó rí ìṣẹ̀lẹ̀ mẹẹdọgbọn mìíràn.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Èkó kéde pé àwọn òṣìṣẹ́ wọn ti ṣe àbẹ̀wò sí àwọn ojúlé tí ó tó 118,000 láàrin ọjọ́ méjì tí wọ́n sì rí iye àwọn ènìyàn tí ó tó 119 tí wọ́n ní àmì tí ó máa ń yọ lára àwọn tí ó ní àjàkálẹ̀ àrùn náà lára.Ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó rí ìṣẹ̀lẹ̀ méjìdínlógún mìíràn.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹrin, ìṣẹ̀lẹ̀ mọ́kàndínlógún ni a rí ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin, ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́jìlélọ́gbọ̀n mìíràn ni a rí ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin, ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́talélógún mìíràn ni a rí ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kọ́kàndínlógún oṣù kẹrin, Àádọ́rin ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun lórí àrùn COVID-19 ni a rí ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó ṣàwárí ìṣẹ̀lẹ̀ mọkandinlogoji mìíràn.Ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin, ìṣẹ̀lẹ̀ mẹ́rìnléláàádọ́rin ni a rí ní ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin, ìpínlẹ̀ Èkó ṣàwárí ìṣẹ̀lẹ̀ méjìdínlọ́gọrin mìíràn.Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin, ọgọ́rin ìṣẹ̀lẹ̀ ni a rí ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kẹẹdọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, Èta-léní-ẹgbẹ̀fà-ẹgbẹ̀fà èèyàn ni ó ní àrùn COVID-19 ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ìhà ti Ìpínlẹ̀ Èkó kò sí àrùn náàni ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2020, Ìpínlẹ̀ Èkó bẹ̀rẹ̀ ìdí ní pẹrẹu.. | wikipedia | yo |
Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó rọ àwọn èèyàn ni ìpínlẹ̀ náà lati dúró sílé, ó si ro àwọn ilé-iṣẹ́ lọlọkan-ò-jọ̀kan lati dáwọ́ iṣẹ́ dúró àmọ́ tí àwọn òṣìṣẹ́ bá lè ṣiṣẹ́ láti ilẹ̀, wọ́n lè tẹ̀ síwájú.. | wikipedia | yo |