cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Lehin na, ni ojo kanna yi ni ile Naijiria fi ofin de irin ajo lo si ati wa lati awon orile ede metala ti won ni isele ajakale arun COVID-19 ti o po julo.. | wikipedia | yo |
Àwọn Orílẹ̀ Èdè yí i ní United States, United Kingdom, South Korea, Switzerland, Germany, France, Italy, China, Spain, Netherlands, Norway, Japan ati Iran.. | wikipedia | yo |
Ni ipinle ogorun won se akiyesi wipe omo orile ede Naijiria kan ti o pada de lati Malasia ni aami aisan ajakale arun COVID-19 sugbon ayewo ti won se ni ojo keji fihan pe koni arun yi.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Kano fidi e mule pe eni meta ti awon se ayewo fun ni ipinle Kano ni ko ni ajakale arun yi.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Eko fi ofin de apejọ awọn Olùjọsìn ti o ba ti kọja Aadọta fun ogbon Ojo.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Ògùn nã fi òfin dé àpéjọpọ̀ tí ó bá ti ju àádọ́ta lọ fún ọgbọ̀n ọjọ́.. | wikipedia | yo |
Ojúbọ Afrika tuntun the New Afrika Shrine dáwọ́ gbogbo ẹtọ won duro titi di igba miran.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Kwara àti Ìpínlẹ̀ Èkó kéde titi gbogbo ile-iwe pa titi di igba miran nigba ti Ipinle Zamfara, Ipinle Sokoto, Ipinle Kat, ipinlẹ Niger, Ipinle Kano, Ipinle Jigawa, Ipinle Kebbi, ati Ipinle Kaduna na ti ile-iwe wọn fun ọgbọ̀n ọjọ bẹrẹ lati ọjọ ketalelogun oṣu Kẹta.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ agbáré àpapọ̀ tí Naijiria Nigeria football Federation dá gbogbo ètò bọ́ọ̀lù wọn dúró fún ose mẹ́rin.ní ọsẹ̀ KỌKÀNble Oṣù kẹta, ìpínlẹ̀ Anambra kede títí àwọn ilé-ìwé wọn pa ati dídáwọ́ ìkọ̀pọ̀ gbangba dúró títí di ìgbàmíràn.. | wikipedia | yo |
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga yíò di títì pa láti ogúnjọ́ oṣù kẹ́ta nígbàtí àwọn ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé girama yíò di títì pa láti ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́ta.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Ògùn sún àkókò tí wọ́n kọ́kọ́ ti fi òfin dé àwọn ilé-ìwé àti àwọn ilé ìjọsìn síwájú di ìgbàìgbà.. | wikipedia | yo |
Ìjọba àpapọ̀ kéde títí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ilé-ìwé girama àti ti alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ pa.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Enugu pàápa pàṣẹ pé kí wọ́n ti gbogbo àwọn ilé-ìwé girama àti ti alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ pa láti ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta.Ní ogúnjọ́ oṣù kẹta, Nàìjíríà tún fi orílẹ̀ èdè méjì kún àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n ti fi òfin dè lórí ìrìn àjò.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì fi òfin dé ìpéjọpọ̀ ayẹyẹ ti Òṣèlú, ti ẹ̀sìn àti ti mọ̀lẹ́bí tí ó bá ti ju ogún ènìyàn lọ.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Èkìtì tún pàṣẹ títí gbogbo ilé-ìwé wọn pa láti ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Nàìjíríà kéde títí àwọn pápá ọkọ̀ òfúrufú ti Enugu, Port Harcourt àti ti Kano lati ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ River na kede titi gbogbo ile-iwe wọn pa ati fifi ofin de gbogbo ayẹyẹ ẹ̀sìn.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Osun fi òfin de eyikeyi ìpéjọpọ̀ gbangba tí o bá ti ju aadọta eniyan lọ lẹsẹkẹsẹ pẹlu àwọn ilé-ìwé, àwọn ilé ijọsin onígbàgbọ àti àwọn Mossalassi.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ipinle Delta kede titi gbogbo ile-iwe won pa lati ojo kerindinlogbon osu keta.Ni ojo kokanlelogun osu keta, ijoba ipinle Nasarawa fidi isele eni marun un ti ayewo so wipe won ko ni arun corona mule.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi kéde titi gbogbo ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama pa.. | wikipedia | yo |
Ile ise oko oju irin ti Naijiria Nigeria Railway Corporation kede ìdáwọ́dúró gbogbo ise won ti won nse fun awon ero oko lati ojo ketalelogun osu keta.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Eko din iye awọn eniyan ti wọn fi ayegba nibi ìpéjọpọ̀ ẹ̀sìn tabi ayẹyẹ ku lati aadọta si ogun.. | wikipedia | yo |
Nàìjíríà kéde títí àwọn pápá ọkọ̀ òfúrufú méjì, tí wọ́n kó ìtí ti pa, ti Abuja àti ti Èkó pa láti ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ṣe àtúnyẹ̀wò ìfòfindè tí wọ́n kọ́kọ́ ṣe lórí ìpéjọpọ̀ gbangba tí kò gbọdọ̀ ju àádọ́ta lọ, sí ìfòfindè pátápátá lórí gbogbo ìpéjọpọ̀ gbangba.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Bàta na pàṣẹ títí gbogbo àwọn ilé-ìwé pa láti ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹta àti gbígbéeselé gbogbo ìpéjọpọ̀ gbàngbà tí ó bá ti ju àádọ́ta ènìyàn lọ.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ipinle Imo na kede titi gbogbo awon ile-iwe pa lesekese.Ni ojo kejilelogun osu keta, ijoba ipinle Edo kede titi gbogbo awon ile-iwe won pa lati ojo ketalelogun osu keta.. | wikipedia | yo |
Ni ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ ẹbọnyín fi òfin dé gbogbo àpéjọpọ̀ gbangba bí i igbeyawo, àpérò, ìsìnkú àti àwọn àpéjọpọ̀ nlá míràn.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Niger kede igbẹle ati fifi ofin de rinrin kiri lati agogo mẹjọ owurọ si agogo mẹjọ aṣalẹ ni ojoojumọ lati ojo kẹẹdọgbọn osu keta.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Kano da gbogbo igbeyin eniyan ni ipinle na duro titi di igbaigba.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers kede isemole onigbadie ni Ipinle na nigbati won ti awon ile iparun pa pẹlu awọn ibi Igba ale, ibi ijosin ibi, ibi ayẹyẹ igbeyawo ati ibi isinku lati ojo kẹrinlelogun Oṣu Kẹta.. | wikipedia | yo |
Ipinle Edo kede fifi ofin de apejọ ti o ba ju aadọta eniyan lọ.. | wikipedia | yo |
The Chief Justice of Nigeria, Tanko Muhammad paṣẹ pe ki gbogbo ilé ẹjọ́ ni ilẹ̀ Nàìjíríà di titi pa lati ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ile Naijiria paṣẹ pe ki gbogbo ẹnubodè di titi pa fun ose merin, ki Igbimọ Isakoso ti Federal.. | wikipedia | yo |
Federal executive Council (fec) si da gbogbo ipade wọn duro titi di igbaigba.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra fi òfin de gbopGbọ́ àpéjọpọ̀ gbangba tí ó bá ti ju ọgbọ̀n ènìyàn lọ.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún fi òfin de ayẹyẹ ṣíṣe bí i ìgbéyàwó, ìsìnkú àti àjọyọ̀.. | wikipedia | yo |
Independent National Electoral Commission kede ìdáwọ́dúró dúró gbogbo ètò wọn fún ọjọ́ mẹ́rìnlá.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó fi òfin de gbogbo àpéjọ òṣèlú, ẹ̀sìn àti àpéjọpọ̀ ní àwùjọ fún ọjọ́ mẹ́rìnlá.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pàá fi òfin dé gbogbo àpéjọpọ̀ ayẹyẹ ṣíṣe tí ó bá ti ju ọgbọ̀n ènìyàn lọ.Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ Yobe kéde títí pa gbogbo ilé-ìwé wọn láti ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Àjọ ti ó n dari ètò ìdánwò àṣewọlé si àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Joint Admission and Matri Board da gbogbo iṣẹ́ wọn dúró fún ọ̀sẹ̀ méjì.. | wikipedia | yo |
Nigerian Senate sun àpérò won siwaju di ojo keje osu kerin, nigbati ile asofin kekere.. | wikipedia | yo |
Nigerian House of Representative sun àpérò wọn síwájú di igbaìgbà.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo din iye àwọn ènìyàn tí wón gbà láàyè láti péjọ ní gbàngbà kù láti àádọ́ta sí ogun, wón sì tún ti gbogbo àwọn ọjà pá sísi àwọn ọjà tí wón ń ta oúnjẹ, oògùn àti àwọn nkan koṣeemani nìkan ni wón gbà láàyè láti ṣiṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Kaduna fese re mule pe awon eniyan meta ti won furasí pe won ni arun Corona ni koni leyin ti won ti se ayewo won.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínle Nasarawa pàṣẹ pé kí wọ́n ti gbogbo ilé-ìwé pa lẹsẹkẹsẹ.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun fi òfin dé Ọjà níná lọ́sẹ̀ẹsẹ̀ títí di ìgbàigbà.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Eko paṣẹ pe ki gbogbo awọn ọja wa ni titi pa lati ojo kerindinlogbon osu keta sugbon ijoba fi aaye gba awon ti won nta ounje, oogun, omi, ati awon nkan koṣeemani miran.. | wikipedia | yo |
Kéde sísun ètò ìdánwò àṣewọlé ti ọdún 2020, tí ó yẹ kí ó wáyé ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, sí àwọn ilé-ìwé ìjọba mẹ́rìnlélọ́gọ́rùn tí wọ́n yà sọ́tọ̀, síwájú di ìgbàìgbà.. | wikipedia | yo |
Ijọba Ipinle Enugu fi ofin de gbogbo igbẹjọ ayẹyẹ ati Oṣelu ni ipinlẹ na.. | wikipedia | yo |
Fi òfin de gbogbo iṣẹ́ wọn káká ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Delta fi òfin de gbogbo àpéjọ ayẹyẹ ṣíṣe tí ó bá ti tó ogún ènìyàn tí ó fi mọ́ ìsìnkú àti ãjọ́sìn gbangba àwọn onígbàgbọ́.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún pàṣẹ pé kí gbogbo ilé ìgbafẹ́ àti ilẹ̀ ìwòran wà ní títì pa lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó pàṣẹ pé kí gbogbo ilé ìtajà di títì pa lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ fún ọjọ́ méje.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun fi ofin de ile ipade ẹgbẹ ati ile ọti fìyàtọ̀si awọn ibi itaja ounjẹ, omi ati oogun.. | wikipedia | yo |
paṣẹ pe ki won ti awon ile ijosin ati awon ile itaja pa fìyàtọ̀sí awọn ti o nta ounje, oogun ati awon ohun koṣeemani.ni ọjọ́ọ́ karundinlogbon osu keta, ijoba ipinle Rivers kede titipa Ẹnubodè Ojú Omi, ti ofurufu ati ti ori ile ti o wole ati eyi ti o jade ni ipinle na bẹrẹ lati ojo kerindinlogbon osu keta.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ kogi nã kéde títipa ẹnubodè ojú omi àti tí orí ilẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun paṣẹ pe ki awon ti won n fi alùpùpù se iṣẹ ni ipinlẹ na dawo iṣẹ wọn duro lati ojo kerindinlogbon osu keta.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún dín iye àpéjọpọ̀ ènìyàn ní ìgboro kù sí márùn ún.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì fi òfin dé Ọjà Títà yàtọ̀ sí àwọn tí ó ń ta nkan tí ó ṣe pàtàkì bí i oúnjẹ, omi, oògun, àti àwọn tí ó ń ṣètò àwọn ẹ̀rọ fún ètò ìlera.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Kwara fi ofin de awọn ọkọ akero, wọn si tun ti awọn masfojú ati awọn ile ijosin onigbagbọ pa.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun ti awon oja ti o yato si awon ti o n ta ounje, oogun ati awon nkan koṣeemani pa.. | wikipedia | yo |
Ipinle Kano na kede titipa Ẹnubodè Oju ofurufu ati ti ori ile ti o wo Ipinle na ati eyi ti o jade bẹrẹ lati ojo ketadinlogbon osu keta.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Bauchi kede titi awon ile itaja pa lati ojo kerindinlogbon osu keta yato si awon to n ta ounje ati oogun.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Abia fi ofin de ayeye isinku ati igbeyawo ṣiṣe ti o ba ti ju ogbon eniyan lọ.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún fi òfin de akitiyan ẹ̀sìn tí ó bá ti ju aadọta eniyan lọ fún ọgbọ̀n ọjọ́.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Imo paṣẹ ki wọn ti awọn ile itaja pataki ni ipinlẹ na pa lati ojo kejidinlọgbọn osu kẹta.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún ti Ẹnubodè Orí Ilẹ̀ pa tí wọ́n sì ńṣe àyẹ̀wò fún àwọn tí wọ́n bá wọlé.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Delta kéde títí àwọn ẹnubodè wọn pa fún ọ̀sẹ̀ méjì àkọ́kọ́.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun kede titi pápákọ̀ ofurufu ti inúpe pa bẹrẹ lati ojo ketadinlogbon osu keta; ẹnubodè ori ile bere lati ojo kokandinlogbon osu keta ati awon ile itaja bere lati ojo kerin osu kerin ti won si pase fun awon ti won n ta ounje ki won ma a tàwọn ni agbegbe ile won.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún pàṣẹ kónílé ó gbélé bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kíní oṣù kẹrin ṣùgbọ́n àṣẹ yí yọ àwọn ènìyàn tó ń pèsè àwọn nkan pàtàkì bí i ètò ààbò, ètò ìlera, àwọn ilé ìtajà òògùn, àwọn tó ń pèsè omi, àwọn panápaná, àwọn oníṣẹ́ mọ̀nàmọ́ná, àwọn oníròyìn àti àwọn ilé-iṣẹ́ tó ń risi ètò ìkansíara ẹni sílẹ̀.Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ Ebonyí kéde pé kí wọ́n ti àwọn ẹnubodè wọn pa bèrè lati ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ṣùgbọ́n wọ́n fi ààyè gba àwọn ọkọ̀ tó ngbé oúnjẹ, àwọn ohun èlò ìkólẹ̀, àwọn ń kan èlò ìlera àti àwọn aláìsàn tí ó ń lọ gba ìtọ́jú.. | wikipedia | yo |
Ijoba apapo ile Naijiria paṣẹ titi awon pápákọ̀ ofurufu ati awon Ẹnubodè ori ile pa fun ose merin.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Rivers kede titi awon oja pa ni ipinle na lati ojo kejidinlogbon osu keta.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ jìgáwá pàṣẹ kí wọ́n ti àwọn ẹnubodè wọn pa láti ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Akwa Ibom pase titi awon Ẹnubodè won pa sugbon awon oko ti o nko ounje ni won gba ki won wole.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ yi tun sọ fun awọn oṣiṣẹ wọn ki wọn fidi mole fun ose kan bẹrẹ lati ogbon ojo osu keta.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún kéde pé kí pápákọ̀ òfúrufú ìpínlẹ̀ wọn, Ibom Air, dáwọ́ gbogbo iṣẹ́ ìrìnàjò ọkọ̀ òfúrufú wọn dúró láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Kaduna gbe ofin kónílé o gbele kale ni Ipinle Kaduna, won si pase ki gbogbo olugbe Ilu fidimo ile won lesekese fìyàtọ̀si awon to nse ise pataki bi i awon osise ilera, awon osise panapana ati awon osise aláàbò.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún pàṣẹ pé kí wọ́n ti gbogbo ilé iṣẹ́ olóko ati àwọn ibi ìjọ́sìn pa.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún fi òfin de àwọn ayẹyẹ igbeyawo àti pípéjọpọ̀ ṣe ayẹyẹ.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ ṣòkòtò kéde títí àwọn ẹnubodè orí ilẹ̀ wọn pa fún ọ̀sẹ̀ meji bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ṣùgbọ́n wọ́n fi ààyè gba àwọn ọkọ̀ tí ó nkó oúnjẹ àti àwọn ń kan èlò ìlera tí ó ṣe pàtàkì.. | wikipedia | yo |
Àwọn olùsósó olú-ìlú ilẹ̀ Nàìjíríà fi òdiwọ̀n sí gbogbo akitiyan okóòwò, ní ìpínlẹ̀ nã, sí wákàtí mẹ́ẹ̀dógún ní ojoojúmọ́ bẹ̀rẹ̀ láti aago mẹsan an àṣálẹ sí aago mẹ́fà òwúrọ̀.Ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pàṣẹ kónílé ó gbélé.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì fi òfin dé ìrìnàjò láti ìpínlẹ̀ kan sí ìpínlẹ̀ kejì yàtọ̀ sí àwọn ọkọ̀ tí ó ń kó oúnjẹ, òògùn àti epo Enboodò bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta nígbà tí wọ́n tún dín iye àwọn ènìyàn tí wọ́n gbà láàyè ní ibi ayẹyẹ kù láti ọgbọ̀n sí mẹ́wàá.. | wikipedia | yo |
Ipinle Oyo tun kede pe gbogbo ọja yio di titipa lati ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n Oṣu Kẹta ṣùgbọ́n àwọn ti o n ta ọja ti o tètè ma n bàjẹ́ ni wọn yà sọ́tọ̀.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun kéde titi ẹnubodè wọn pa lati ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún kéde títí àwọn ọjà tí ó ṣe pàtàkì pa yàtọ̀ sí àwọn ọjà tí wọn ń ta oúnjẹ àti oògùn.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Katwo kede titi awọn ẹnubodè wọn pa lati ọjọ kejidinlọgbọn osu keta sugbon wọn fi aaye gba awon oko ti o n gbe epo pésẹ̀odò ati ounjẹ ki wọn wọle lẹhin ti wọn ba ti ṣe ayewo wọn.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Enugu kéde titipa ẹnubodè wọn ati gbigbe ọkọ lati ipinlẹ kan lọ si ekeji lati ojo kokanlelogbon Oṣu Kẹta yato si awon ọkọ oṣiṣẹ olutọju alaisan.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Nasarawa fi òfin de gbogbo ìpéjọpọ̀ ayẹyẹ àti ti ẹ̀sìn tí ó bá ti ju àádọ́ta ènìyàn lọ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún kéde fífi òdiwọ̀n sí gbogbo lílọ àti Bíbọ̀ sí ìpínlẹ̀ nã.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Niger fi ofin de lilo ati bíbọ àwọn ọkọ lati ipinlẹ kan si ipinlẹ keji yàtọ̀ si àwọn ọkọ ti o n gbe ounjẹ ati àwọn nkan miran ti o ṣe pataki.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Zamfara kede titi awon Ẹnubodè won pa bẹrẹ lati ojo kejidinlogbon osu keta, odun 2020.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Bàtata kéde tìbọ̀ àwọn ẹnubodè tí ó gba orí omi àti orí ilẹ̀ wọ ìpínlẹ̀ wọn wọlé lẹ́sẹkẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́ta, ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra kéde títìpa àwọn ọjà mẹ́tàlélọ́gọ́ta wọn tí ó ṣe pàtàkì, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta, fún ọ̀sẹ̀ méjì ṣùgbọ́n wọ́n fi ààyè gba àwọn ọjà tí wọ́n ń ta oúnjẹ àti oògùn.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ipinle Abia kede titipa awon ẹnubodè ati oja won fun ose merin bere lati ojo ekíní osu kerin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún pàṣẹ fún àwọn ará ìlú láti fìdí mọ́lé ṣùgbọ́n wọ́n fi ààyè gba àwọn tí ó ń ta oúnjẹ nìkan láti ta ọjà.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ ìmọ̀ fi òfin de àwọn ayẹyẹ ìgbéyàwó, ìsìnkú àti ti ẹ̀sìn lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún pàṣẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ wọn láti dáwọ́ iṣẹ́ dúró lẹ́sẹ̀kes yàtọ̀ sí àwọn tí iṣẹ́ wọn ṣe pàtàkì tí ìjọba sì fọwọ́ sí.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn Kéde titipa àwọn ẹnubodè wọn fún ọ̀sẹ̀ méjì àkọ́kọ́ láti ọjọ́ Kọkàndínlógbọn oṣù kẹta ṣùgbọ́n wọ́n fi ààyè gba àwọn ọkọ̀ tí ó ń gbé àwọn òṣìṣẹ́ tí iṣẹ́ wọn ṣe pàtàkì bí i àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò, àwọn olùtọ́jú aláìsàn, àwọn tó ń ta oúnjẹ àti àwọn tí ó ń ta epo rupésún.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Cross River fi òfin de gbogbo àpéjọpọ̀ ẹ̀sìn tí ó bá ti ju ènìyàn márùn ún lọ.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi kéde fífi òdiwọ̀n sí ìjáde àti ìwọlé sí ìpínlẹ̀ nã lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |