cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Isah Misau (tí a bí ní ọdún 1970 ní Bauchi, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Lọwọlọwọ, oun ni Alaga Igbimọ ti o nri si oro nipa awon omo ogun ori omi ni ile asoju Agba ti ile Naijiria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé Ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ní Nàìjíríà tí ó ń sojú aringbungbun tí Ìpínlẹ̀ Bauchi.Èkó àti iṣẹ́ Misau kọ́ ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga olókìkí ti Ahmadu Bello University, ní Kàdúná níbití ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ gba oyè àkọ́kọ́ (BSc) nínú Èkó nípa ìṣàkóso òwò (Business Administaration) ní ọdún 1997..
wikipedia
yo
Bakanna ni odun 2010, o tun gba oye eleekeji (MSc) ninu imo lori agbowo (Law Enment) lati ile eko giga Ahmadu Bello University bakanna Isah Misau bẹrẹ iṣẹ rẹ ni odun 2000 gege bi oluṣakoso osise (Administrative Officer) ni ile ise olopa ti orile ede Naijiria (Nigeria Police Force) ti o si sise gege bi olopa fun odun mewa ki o to di wipe o kowe fi ise sile..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, Misau fi ìfẹ́ hàn láti díje lọ sí ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú Àgbà láti lọ ṣojú aringbungbun ti Ìpínlẹ̀ Bauchi..
wikipedia
yo
Misau yege nínú ìdìbò yí ní Oṣù Kẹta ọdún 2015 nígbà tí ó borí bọ́ọ̀lù nígi, ẹni tí ó jẹ́ igbákejì olùdarí ọmọ ẹgbẹ́ tí ó pọ̀ jùlọ.Àríyànjiyàn ní Oṣù Kẹjọ ọdún 2017, Misau kojú àwọn ẹ̀sùn tí ó lágbára láti ọ̀dọ ọ̀gá àgbà pátápátá fún àwọn ọlọ́ko (IGP), Ibrahim Kpotun Idris..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára wọn ni ẹ̀sùn ti Ọ̀gá àgbà pátápátá fún àwọn ọlọ́ fi kan Misau pé ó jẹ́ ẹni tí ó ma nta tí ó sì ma nra Igbó (Indian Hemp) Lorekore..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fi ẹ̀sùn kan Misau pe níṣẹ́ ni o sa nínú iṣẹ́ ọlọpa àti wípé ó ṣe é ṣe kí ó jẹ́ wípé ó ṣe ayédèrú lẹ́tà ìfẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe àwọn àfihàn yí ní àkókò ẹ̀sùn ẹjọ́ ìṣòwò ] tí wọ́n fi kan Ọ̀gá àgbà pátápátá fún àwọn Ọlọpa..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kesán Ọdún 2017, ìgbìmọ̀ fún àwọn ọlọpa fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ pé lẹ́tà Ìfẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́ tí Misau fi sílẹ̀ kì í ṣe ayédèrú̀ó.àwọn ìtọ́kasí àwọn ọmọ ilé ìwá ilẹ̀ Nàìjíríà Ọjọ́ìbí ní 1970àwọn ní 1970.. Gbogbo ènìyàn
wikipedia
yo
Kíndìnrín jẹ́ àwọn ẹ̀yà ara inú méjì tí ìrísí wọn dà bí ẹwà, tí a lè ṣalábàápàdé rẹ̀ ni ara gbogbo ẹranko elégungun..
wikipedia
yo
Àwọn mẹ́tatẹ̀mí yí wà ní apá ọ̀tún àti apá òsì ní ìsàlẹ̀ aya..
wikipedia
yo
àwọn kíndìnrín wọ̀nyí ma ń gba ẹ̀jẹ̀ sára láti ara iṣan tí ó so pọ̀ mọ́ ọkàn tí wọ́n ń pè ní renal arteriée..
wikipedia
yo
Kíndìnrín kọ̀ọ̀kan ni ó tún so mọ́ iṣan mìíràn tí wọ́n ń pè ní (Uureter), iṣan yí ni ó ń ran àwọn kíndìnrín yí lọ́wọ́ láti máa gbé itọ́ láti inú kíndìnrín lọ sí inú ilé tàbí àpò ìtọ̀ tí wọ́n ń pè ní (Blaley). Iṣẹ́ Kinbọ́ọ̀lù kíndìnrín kọ̀ọ̀kan ni a ti rí àwọn iṣan wẹ́wẹ́we i orúkọ wọn ń jẹ́ (Nenephron) tí ó tó míìnu kan níye, tí wọ́n kọ́ tẹ́ẹ́rẹ́ ju irun orí lọ tí ojú lásán kò le rí, àyàfi pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Ìwọgbé (Jámánìth), tí àwọn iṣan wẹ́wẹ́we wọ̀nyí náà tún gbọ́mọ pọ́n..
wikipedia
yo
Nínú àwọn ìṣàn wẹ́wẹ́ yìí ní isàyípadà ní omi àti ẹ̀jẹ̀ tí kò wúlò fún ara mọ́ ti ma ń yí padà sí itọ́ tí yóò sì bá ojú ara ọkùnrin àti obìnrin jáde láti ilé ìtọ̀..
wikipedia
yo
Bákan náà ni kíndìnrín tún ń kópa pataki ninu ṣíṣètò ati dídarí omi,ẹ̀jẹ̀, ásíìdì, ati yíyọ àwọn ohun tí kò dá kúrò lára..
wikipedia
yo
Kíndìnrín ni a lè pè ní àṣẹ tí ó ń jó gbogbo ohun bíi omi, ẹ̀jẹ̀, àti ásíìdì àti àwọn nkan mìíràn tó bá gba ọ̀dọ̀ rẹ̀ kọjá .Àwọn ìtọ́ka síẹ̀yà ara..
wikipedia
yo
Iṣan ni okùn ara tí ó rọ jùlọ tí a lè rí ní ara pupọ ninu ẹranko..
wikipedia
yo
Nínú iṣan kọ̀ọ̀kan ni a ti rí protein, ACtin àtimyosìn tí wọ́n gba orin ara wọn kọjá nínú iṣan lọ́hùn ún, àwọn èròjà wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ kí iṣan le, rọ tàbí kí ó wà láàrín méjì gẹ́gẹ́ bí ipò tí ara bá wà lásìkò kan.Iṣẹ́ iṣanLAAMra iṣẹ́ àwọn iṣan inú ara ni kí ó ràn wá lọ́wọ́ láti lè rin, gbéra tàbí lọ láti ibìkan sí ibòmíràn lásìkò kan..
wikipedia
yo
Iṣan ló má ń ṣiṣẹ́ ìbójútó ipò ara níbi ìdúró, ìbẹ̀rẹ̀, ìjókòó ati nínà sílẹ̀ gbalaja, tabi nígbà tí a bá sùn sílẹ̀, iṣan ni ó ń ṣàkóso ìgbòkègbodò ati lílọ bíbọ̀ ara..
wikipedia
yo
O tún ma ń jẹ́ kí àwọn bí ẹ̀jẹ̀ ati omi o ríbi gbà káàkiri inú ara..
wikipedia
yo
Skẹ̀lẹ̀tal muscles in turn can be Divided into fast and slow Twitch fibers.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ẹwà ni ikán lára àwọn igi eléso tí ó ń sọ ohun jíjẹ ẹlẹ́yọ, tí ènìyàn tàbí ẹranko lè jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ.Oríṣi ọ̀nà tí a lè gbà jẹ́ ẹwàọ̀nà tí a lè gbà láti ṣe tàbí jẹ ẹ̀wà pọ̀ kògan-rere..
wikipedia
yo
A lè fi ẹwà ṣe ọbẹ̀ ìbílẹ̀ tí a ń pè ní gbegirigbì àti kíkórè ẹ̀wàyàtọ̀ sí àwọn oúnjẹ akẹgbẹ́ ẹ̀wà tókù, ẹ̀wà ní tirẹ̀ jẹ́ ohun eléso tí ó nílò ooru tàbí oòrùn gbígbóná láti dàgbà..
wikipedia
yo
Kí ẹwà tó lè dàgbà débi tí yóo tó kórè, yóo lọ tó ọjọ́ marundinlọgọta sí ọgọta ọjọ́ kí ó tó lè ṣe é kórè lóko..
wikipedia
yo
Níbẹ̀rẹ̀ ìdàgbàsókè rẹ̀, epo tàbí pádi rẹ̀ yóò wà ní àwọ̀ ewé mìnìjọ̀, nígbà tí ó bá tún ìdàgbàsókè díẹ̀ sí, pádi rẹ̀ yóò di àwọ̀ pípọ́n rẹ́súrẹ́sú, nígbà tí àwọ̀ rẹ̀ yóò di dúdú nígbà tí ó bá gbó tán..
wikipedia
yo
Pupọ ẹ̀wà ni o ma ń nílò ìrànlọ́wọ́ igi lnitosi wọn láti fi gbéra sókè, àmọ́, ẹ̀wà ṣẹ̀ṣẹ̀ kìí nílò ìrànwọ́ kankan láti fi dàgbà rárá.Àwọn ìtọ́kasíoúnjẹ elésoàwọn ohun ọ̀gbìn jíjẹ..
wikipedia
yo
Dígí tàbí díńgí ìwọ̀gbé ni ohun èlò kan tí a ń lò láti fi wo àwòrán ara ẹni tí yóò sì gbé àwòrán náà wá fúni gẹ́gẹ́ a ti rí.Oríṣi dígí tí ó dàrú àwọn dígí tí ó wọ́pọ̀ tí a ma ń rí tàbí lọ jùlọ ní Pãngan (Plain Mirror)..
wikipedia
yo
Èkejì ni dígí ẹlẹ́bùú (cirved Mirror), wọ́n ma ń lo dígí yìí láti fi pèsè irúfẹ́ àwọn dígí mìíràn tí a lè fi wo ohun tó bá wé ni.Ìwúlò dìyìngia ma ńun dígí fún Orissarisi nkan..
wikipedia
yo
Lára rẹ̀ ni kí a fi wo ara ẹni yálà ojú tàbí ibi kọ́lọ́fín tí ojú kò le ká lára..
wikipedia
yo
Wọ́n ms ń lo dígí fún wiwo eyín lára ọkọ̀, kéékẹ̀ ológẹ̀rẹ̀, kẹ̀kẹ́ alùpùpù ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
wọ́n ma ń lòó láti fi sẹ́sẹ́ ara ilé.Àwọn Dókítà Olùtọ́jú ẹ̀yin náà ma ń lòó láti fi wo korọ ẹnuwọ̀nwọ́n ń lo dígí láti fi pèsè iléjú èrò ayàwòrán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ìwòrẹ̀ jẹ́ èè ìgbẹ ohun ògbìǹ tí gbogbo ènìyàn ma ń jẹ́ lọ́ka-já jákè-já àgbáyé, paá paá jùlọ ní ilẹ̀ Asia..
wikipedia
yo
Ohun ọgbin yi jẹ́ ọ̀kan gboogi ninu ohun ọgbin ounjẹ ti wọn pese julọ ni agbaye ni iye ( 741.5 milionu tọọnu ni ọdun 2014), lẹ́yìn Ìrèké ati Àgbàdo.
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n ma ń lo ìrèké àti àgbàDO fún Ìpèsè Orissarisi nkan, yàtọ̀ sí JÍJẸ lasán bíi ti ìrẹsì..
wikipedia
yo
ọrisirisi ìrẹsì lo wa, irúfẹ́ eyi ti o ba hu ni agbegbe kan ma n da lori ile ati oju ojo agbegbe naa..
wikipedia
yo
Ìrèké, jẹ igi tere gíga tí o má dùn minsin-sìnsìn nígbà tí a bá gé sẹ́nu..
wikipedia
yo
O sábà ma ń hù jùlọ nibi tí ilẹ̀ omi rẹ bá wà ní ìwọ̀ntún-wọ̀nsì, òun sì ni wọ́n fi ń ṣe ṣúgà jíjẹ.Ìrísí rẹ̀ ìrèké ma ń ga níwọ̀nn bàtà mẹ́fà sí ogun, o.Ma ń ní kọ́kọ́ ní ìpelel ìpele, tí adùn rẹ̀ sì ma ń dá lórí ìpele kọ̀ọ̀kan láti ìdí..
wikipedia
yo
Ìrèké tun jẹ ọkan lara ebi àgbàdo, ìrẹsì, ọkà bàbà ati bẹẹ bẹẹ lọ.ogbin Ìrèké LágbàáyéÌrèké ni ohun ogbin ti wọn gbin julọ ní àgbáyé pẹ̀lú iye 1.8 bilionu tọọnu ní ọdún 2017, nígbà tí orílẹ̀-èdè Brazil kọ́ ìdá ogójì nínú ìpèsè ọ̀gbìn ìrèké lọdún náà.Ẹ̀yà ìrèké tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ (Saccha officina ) tí iye rẹ̀ tó ìdá àádọ́rin ni wọ́n fi ń pèsè ṣúgà jùlọ.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ohun ọ̀gbìn jíjẹ..
wikipedia
yo
Èèwọ̀ ni ohun àìgbọ́dọ̀ ṣe, ìyẹn ìwà èérí tí òrìṣà kórìíra..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹòrìṣàòrìṣà Ọbàtálá Ọbàtálá lòdì sí ìdọ̀tí tàbí nǹkan ẹ̀gbin, ìwà èké, ìwà àìṣòdodo, àti ọ̀dàlẹ̀.Òrìṣà Ṣàngó Ṣàngó kórìíra ìwà olè..
wikipedia
yo
Ará ni ó ń san pa ọ̀lẹ,tí yóò sì gbé ohun tó bá jí lé ní aya.Òrìṣà ogún ogún lòdì sí ìwà irọ́-pípa, èké-ṣíṣe, ẹrú-ṣíṣe àti ilẹ̀-dídá..
wikipedia
yo
Èrèdìí tí wọ́n fi ń fi àmì ogun ṣe ìbúra ní ilé ẹjọ́.Òrìṣà Ọ̀ṣun òrìṣà onínú funfun ní osùn..
wikipedia
yo
Ẹni tí inú rẹ̀ kò bá mọ́ kò gbọdọ̀ dé ìdí òrìṣà ọ̀ṣun...
wikipedia
yo
Iṣẹ́ dé ọmọ aláṣejẹọwọ́ de ọmọ aláṣela òwò ṣíṣe ti a tún mọ si kárà-kátà jẹ́ ọ̀kan pàtàkì ní ara iṣẹ́ ajé àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
èròǹgbà ontàjà ni lati jèrè, nítorí ‘èrè ni ọmọ ọlọ́jà ń jẹ́ọkùnrin
wikipedia
yo
ọwọ́ ṣíṣe n lé ìṣẹ́ àti òṣì dànù, a sì sọ ni di olówó.3..
wikipedia
yo
Ó ṣokùnfà àjọṣepọ̀ láàárín ẹ̀yà Yorùbá àti ẹ̀yà mìíràn.
wikipedia
yo
Sandra AChums jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti àfọwọ́-ṣàánú ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Hanvirusvirus tabi Orthohantavirus je kòkòrò ẹran fojufoju ti o maa n jẹyọ lára eku..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹran kòkòrò àìfojúrí tí ó máa ṣẹ́yọ lára eku, ṣùgbọ́n kìí ṣe wọ́n ní ìjàmbá kankan..
wikipedia
yo
Eniyan lè kó ẹran kòkòrò fojufoju, Hanvirus láti ara itọ́, irọ́ tàbí imígbé ẹ̀kú..
wikipedia
yo
Èyí lè fa àìsàn ibà tí wọ́n ń pè ní Hantavirus Hemorrhagic Fever with renal syndrome (19552), tàbí èyí tí wọ́n ń pè ní Hantavirus pulmonary syndrome (H£ps), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Hanvirus Caroubenzaldehyde syndrome (HCPps), àwọn àìsàn mìíràn tí ẹran kòkòrò fojudi yìí máa ń fà, kò ì tí ì ṣẹ́yọ lára ènìyàn..
wikipedia
yo
H£ (HPSps) yìí jẹ́ àrùn tí ó maa ń jẹ mọ́ gími nípa fífà oòrùn igbẹ tàbí ìtò eku tí ó ti ní ẹran kòkòrò fojú Hanvirus Sí̀yàn.”Eniyan lè ko àgbákò àrùn ti ẹran kòkòrò ìfojù hànvirus máa ń fa bi ènìyàn bá fara kan igbe eku, ṣùgbọ́n ní pẹ̀lú 2005, ìròyìn gbé e pé ẹkan kan ko àrùn náà lára ẹbi ní gúúsù (South America). Ṣṣẹ̀dá orúkọ yìí, hàn ní ara virus lati ara kan tí wọ́n ń pè ní hàn ní han yàrá Korea, níbi tí àrùn náà ti kọ́kọ́ rẹ̀ tí àwọn ìji.. 2..
wikipedia
yo
Aba tabi abule ni ileto kan ti a kọ ile Isrisi si ti awọn eniyan da silẹ fun gbigbe..
wikipedia
yo
Àbá tàbí abúlé ma ń fẹ́, tóbi tí ó sì ma ń ní èrò púpọ̀ ju ahéré lọ..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, abúlé ló sábà ma ń dàgbà sókè di ìlú ńlá nípa bí àwọn eniyan bá ṣe ń pọ̀ sí..
wikipedia
yo
Kí a tó lè pe ibì kan ní abúlé, ó ní láti jẹ́ wípé iye àwọn ènìyàn tí ó ń gbé níbẹ̀ tó ọgọ́rùn ún sí ẹgbẹ̀rún kan níye..
wikipedia
yo
Pupọ àwọn abúlé tabi abà ni wọ́n ń wà ní ìgbèríko tabi aroko tí wọ́n sì ma ń yan iṣẹ́ ọ̀gbìn láàyò lọ́pọ̀ ìgbà tabi ńká mìíràn gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ ajé..
wikipedia
yo
Àwọn ilé inú abúlé ma ń sábà fún pọ̀ tàbí sún mọ́ ara wọn , èyí sì ni ó ma m mú ìbáṣepọ̀ tó dán mọ́rán wá láàrín àwọn olùgbé ibẹ̀..
wikipedia
yo
Alákàn tàbí àkàn tí wọ́n ń dá pè ní Decd ní èdè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ ẹranko tí ó lè gbé lórí ilẹ̀ àti inú omi..
wikipedia
yo
( = Short, / ​ Goun)Ẹranko yí ma ń gbè nínú Pala Pala keke ilẹ̀ tàbí abẹ́ àwọn ewéko ní etí omi..
wikipedia
yo
Bákan náà ni kò sí ibi tí wọn kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé pátá.Ìrísí rẹ̀alákàn jẹ́ ẹranko tí gbogbo egungun ara rẹ̀ wà ní ìta tí àwọn ẹran rẹ̀ sì sá pamọ́ sí inú ihò egungun ara rẹ̀..
wikipedia
yo
O saba ma n ni ese mefa; meta lọ́tùn ún meta losi, bẹẹ ni o ni kini kan bi iledìí kokan lọ́tùn ati losi, ti o si tun ni owo meji niwaju ti owo naa si tun ni ẹmu (pincer) ti o fi ma n dáàbò bo ara re lowo ewu.Ori Akan to Warissarisi akàn ti o wa ni o ni orukọ ti won n o won ni agbegbe ti won ba wa ni orile agbaye..
wikipedia
yo
Àjàkáyé-àrùn erankón ọdún 2019-2020 tàbí ajakaye-arun COVID-19 ní Àjàkáyé ajakaye-arun tí ó ṣẹlẹ̀ ní àárín ọdún 2019 àti 2020 tí ó ń tàn káàkiri orílẹ̀ ède gbogbo àgbáyé lọ́wọ́lọ́wọ́..
wikipedia
yo
KÒKÒRÒ àìlèfojúrí afàìsàn korona tí ó ń ṣàbá fún gími owó kejì (SARS-CoV-2) ló sokunfa òtilè àrùn náà..
wikipedia
yo
Agbegbe Wuhan, ni ilu hubei, lorilẹ-ede China ni ajakale arun yii ti koko farahan lóṣù kejila odun 2019, ti o sin ti di nnkan ti ajo ti o n ri si eto ilera ni agbaye, World Health Organization ti kede re gege bi arun pajawiri gbogboogbo lagbaaye ti won gbodo moju to..
wikipedia
yo
Títí di ọjọ́ kẹwàá oṣù ó ti ọdún 2020, ó ti ju ènìyàn 118,000 tí ó ti kó àrùn yìí káàkiri gbogbo àgbáyé, tí 5,800 nínú wọn jẹ́ èyí tí wọ́n kà sí pé àrùn náà ti wọ̀ wọ́n lára jù..
wikipedia
yo
Ó ti ju orílẹ̀-èdè aadọfa (115) tó ti kàgbákò ibesile ajakale-arun ẹran korona lodun yìí, pàápàá jùlọ àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè China, Italy, South Korea àti ìran..
wikipedia
yo
Ó ti ju ènìyàn ìgbàlélẹ́gbẹ̀rún, 4,200 tí àrùn yìí ti pa ní ìfọnnáfóṣù, ó tó ènìyàn ọgọ́rùn-ún-lé-lẹ́gbẹ̀ta, (3100) tí wọ́n kú ní orílẹ̀ èdè China nìkan, àti ẹgbẹ̀rún kan ènìyàn káàkiri àwọn orílẹ̀ èdè op kú káàkiri àgbáyé..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà, ó ti ju eniyan mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ẹgbẹrun (64,000) tí wọ́n ti mórí bọ́ ninu àjàkálẹ̀ àrùn yìí..
wikipedia
yo
èrà yìí máa ń ràn láti ara ẹnìkan sí ẹlòmíràn nípa èémí ipòjáde bí a bá ń wúkọ́ tabi bí a bá ń sín.Àkókò tí eniyan bá kó àrùn yìí ati ìgbà tí ó máa farahàn má ń sábà máa ń tó ọjọ́ marun-un, ṣugbọn nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó lè tó nǹkan bí ọjọ́ meji sí mẹrinla..
wikipedia
yo
Àwọn Amin ìfarahàn rẹ̀ ṣáá a máa ń wá bí, àìsàn ibà, ìkó wúwú, ati àìlèmí kanlẹ̀..
wikipedia
yo
Ipeleke arun yìí máa ń fa àrùn ẹ̀dọ̀fóró, àti ìnira èémí..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ìwádìí ìjìnlẹ̀ ń lọ lórí rẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Igbìyànjú láti mójú tó àwọn àmìn ìfarahàn rẹ̀ ni àwọn oníṣẹ́ ìwòsàn ń ṣe.Àwọn ọ̀nà tí wọ́n là kalẹ̀ láti dẹ́kun àrùn yìí fífọwọ́ déédé, jíjìnnà sí ara ẹni, pàápàá jùlọ ẹni tí ó bá ń ṣàìsàn tàbí fura sí pé wọ́n ní àrùn yìí àti ìyáraẹnisọ́tọ̀ ẹni tí ó fura pé òun ni àrùn yìí.Lára àwọn ọ̀nà ìdẹkùn mìíràn tí wọ́n ń gbà láti dẹ́kun jíjákalẹ̀ àrùn yìí káàkiri àgbáyé ni dídẹ́kun ìrìn-àjò, ìyá Soto ẹni-afurasi, òfin kónílé-ó-gbélé, àti títí àwọn ilé-ìwé pa..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú bíi hubei lórílẹ̀ èdè China ati gbogbo orílẹ̀ èdè Italy ló wà ní ìyàsọ́tọ̀-àmójútó lọ́wọ́ báyìí, bẹ́ẹ̀ náà òfin kónílé-ó-gbélé ń lọ lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè China ati South Korea; bẹ́ẹ̀ náà, àyẹ̀wò fínnífínní ní pápákọ̀-òfuurufú ati ìdíkọ̀ ọkọ̀ Ojúrin;àti ìmọ̀ràn ìrìn-àjò ní ìlú tabi agbègbè tí àrùn yìí bá ti ń jàkalẹ̀..
wikipedia
yo
Ile-iwe titipa patapata ni gbogbo orile-ede tabi agbegbe ti arun yii ti seyo ni awon orile ede miiran, eyi ti se ojo fun ode ọọdunrun Milionu (300 million) awon akekoo jakejado agbaye.Àkóbá nla miiran ti ibẹ̀sile ajakale-arun ẹran korona lodun 2019-20 yii ni ìfàsẹ́yìn eto oro-aje ati ìbágbépọ̀, bee naa Ibesile ajakale-arun ẹran korona lodun 2019-20 ti fa elẹ́yàmẹyà ati ija-a-ọfẹ-o-nílùú wa si awon omo orile-ede China ati awon omo iran ila Oorun Asia, bakan naa iroyin Oroko lori ikanni ayelujara nipa ibesile ajakale-arun ẹran korona lodun 2019–20 ati awon aríjẹ-nídìí ibaje lori ajakale arun naa ko gbeyin.Wo ti arun yii fi n jakaletiti di ojo kejila osu keta odun 2020, o ti ju eniyan 126000 ti o ti ko arun yii kaakiri gbogbo agbaye, iwoye wa pe won ko jabo to bi arun yii se n yaṣẹ paapaa julo awon ti amin ifarahan si se ni KÚ osu kejila lodun 2019, awon onimo ilera kede pe aisan ẹ̀dọ̀fóró seyo si awon eniyan ni Wuhan, nibi hubei, LÓRÍLẸ̀-ede China sugbon ti won ko mo ohun ti o sokunfa re..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ pédì òràpọ̀ ògbẹde yìí, wọ́n tọpinpin rẹ̀ oja kan tí wọ́n ti wọ́n ń pè ní hu Seable whole market, wọ́n sìn lọ́lẹ̀ pé lati ara Zẹ̀ga ní kòkòrò foju tí ó ń fa àìsàn náà ti ṣe wá.kòkòrò fojú yìí tí ó fa òràru ògbẹga ní wọ́n ń pe ní SARS-2, kòkòrò ìfojù Tuntun ti o fara pe kòkòrò gbádùn pé láti ara àdán, Pan Coronadọ̀ of SARS-05.. and SARS-CoV.. and SARS * ní pẹ̀lú pẹ̀lú pẹ̀lú pẹ̀lú ẹni tí ó maa ìrà * * ní wọ́n maa ní wọ́n * ti ń pe ní wọ́n * * ní wọ́n t ní wọ́n maa ẹ̀fà kan * ti àwọn èro tún fi ní wọ́n fa òṣẹ ní wọ́n sin ni ọdún ẹ̀ru ní pẹ̀lú ẹni ní ọdún rẹ̀ ní ó fara iriǹro ní wọ́n * * ní wọ́n * ní ọdún Ọ̀rànu òrà sí àwọn pé ní pẹ̀lú ijo àkọ́kọ́ pé wọ́n ní wọ́n maa sí wọ́n maa sí wọ́n ti wọ́n sí wọ́n ní wọ́n ní ọdún yìí pé omi yìí tí wọ́n ti tipa yìí ní ó ń fi ń pe ni wọ́n maa kan * ní ti ń pè pé lati ara Z ní .. ] tí ó ń pe sí òṣẹ ní ó fa àwọn ní òwà ní wọ́n ń pe
wikipedia
yo
Ìgbàgbọ́ wa pé, ó ṢEÉ ṣe kí kòkòrò àìfoju yìí wá láti ara àwọn ẹ̀yà àdán tí wọ́n pè ní Rhinvvi. Àìsàn yìí kọ́kọ́ ṣẹ́yọ ní ọjọ́ kìíní Oṣù kejìlá ọdún 2019, láti ara ẹnìkan tí kò dé ọjà ọ̀́rikòrí okùn, (Hugúngún Seafood àti Market) tàbí ní ìbápọ̀ kankan pẹ̀lú àwọn ogójì àwọn mìíràn tí àyẹ̀wò ọwọ́ àkọ́kọ́ ṣàfihàn pé wọ́n ní kòkòrò àìfoju náà..
wikipedia
yo
Ninu ayewo owo akoko, ipin meji ninu meta ni ayewo fihan pe won ìbáṣepọ̀ pelu wẹ̀we (Talita market), ti o maa n ẹrán lóòyẹ̀.Àjọ Ìlera Àgbáyé World Health Organization (WHO) kede ajakale àìsàn naa gege bi ajakale arun gbogboogbo ti o nilo imojuto pajawiri ni glutamic osu osere odun 2020.Oludari Àjọ Ìlera Àgbáyé, who, Ogbeni Tedros Adhanọ̀m, gbóríyìn fun ijoba orile ede China fun akitiyan ati igbese won lati ri i pe ajakale arun ti kòkòrò foju korona n fa ko tan kale ju bo se ye lo lórílẹ̀-ede naa, bi o tile je pe o n ja ran.”Miyìn ni awon agbegbe orile-ede miiran..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àrùn yìí, iye àwọn ènìyàn tí ó ń lùgbàdì àìsàn yìí tó ìlọ́po méjì láàárín ọjọ́ méje àti abo..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù kìíní ọdún 2020, kòkòrò dífoju yìí ti jákalẹ̀ dé àwọn agbègbè China, ọdún hunyún, tí ó jẹ́ ayẹyẹ àìsùn Ọdún Tuntun ní China, tí wọ́n ṣe ní ìlú Wuhan ló ṣe àkóbá fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n lùgbàdì àìsàn yìí, nítorí pé ilú Wuhan ni ilú tí ìgbòkègbodò ọkọ ti gbòde jù ní China..
wikipedia
yo
Loyejo osu kìíní odun 2020, orile-ede China kede ogoje eniyan ti won lùgbàdì arun yii lọjọ kan soso, ati eniyan meji miiran ni Beijing, pelu enikan ni Shenhenlọ́jọ́. kerindinlogbon osu keji odun 2020, ajo ilera agbaye, who kede idi ku ninu awon ti o n ko arun yii ni China, sugbon ti ajakale arun naa gbinaya ni orile-ede Italy, iran ati South Korea..
wikipedia
yo
Iye awon eniyan tuntun ti o n ko arun naa ni orile ede miiran ti ju ti China lo.pínnísín ni iye awon omode ti ayewo ti fihan pe won ni ajakale arun yii titi di ojo kerindinlogbon osu keji odun 2020..
wikipedia
yo
Ìkéde kan láti ọwọ́ Àjọ Ìlera Àgbáyé WHO fihàn pé ìdá 2.4 ni àwọn ọmọdé tí ọjọ́ orí wọn kò ju mọ́kàndínlógún lọ ló ní àrùn COVID-19 yìí káàkiri àgbáyé.Iye àwọn tó ti kú láàárín ọjọ́ mẹ́fà sí mọ́kànlélógójì, ti Àmin àrùn náà ṣẹ́yọ àti àsìkò tí àrùn COVID-19 hàndé ni àwọn tí wọ́n lùgbàdì rẹ̀ ń kú, àgbálọgbábọ̀, ọjọ́ mẹ́rìnlá .
wikipedia
yo
Titi di ojo merinlelogun osu kejo odun 2020, o ti ju eniyan 800,000 ti arun COVID-19 ti pa.gege bi NHC ti orile ede China ti so, àgbàlagbà ni o poju ninu awon ti arun naa pa..
wikipedia
yo
Ó tó ìdá ọgọ́rin, 80% àwọn àgbàlagbà tí ọjọ́-orí ti kọjá ọgọ́ta tó kú, àti ìdá márùndínlọ́gọ́rin àwọn tí wọ́n ti ní àìsàn mìíràn lára tẹ́lẹ̀, pàápàá jùlọ àìsàn ọkàn, Cardiovascular Diseases àti ìtọ̀ ṣúgà, Diabetes.Ẹni àkọ́kọ́ tí àìsàn yìí pa kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kìíní ọdún 2020 ní ìlú Wuhan.Ẹlòmíràn tó kú ní orílẹ̀ èdè mìíràn yàtọ̀ sí China kú ní orílẹ̀-èdè Philippines, ẹlòmíràn tí ó tún kú, tí kì í ṣe láti ilé Asia kú ní Faransé.Lẹ́yìn China, ó ti ju ènìyàn méjìlá..
wikipedia
yo
Méjìlá ló tí wọ́n ti kú ní ìran, South Korea, àti Italy..
wikipedia
yo
Bakan naa, opolopo eniyan iroyin ti fidi re mule pe won ti ku iku arun korona apa ariwa Amerika (North America), Australia, San Oo, Spain, Iraq, ati United Kingdom..
wikipedia
yo
Ìwé ìròyìn Daily nkk jáná pé àwọn ọmọ-ogun tó ti ju igba (200) ní àrùn korona ti pa lórílẹ̀-èdè North Korea.Àwọn Àmín àti ifarahan Kosi àmìn kan pato tí kòkòrò àìfoju korona, COVID-19 maá n gbé yọ lára ẹni tí ó bá kó o..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó bá kọ́ ọ lè máà ní àmìn kankan tàbí kí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní saìlera bí i ikọ́, ìba, àìmí kanlẹ̀, ara rírọ́, àìlókun, àwọn Àmín àti ìfarahàn rẹ̀ ló wà nínú tabili yìí.L.Bí àrùn yìí bá ti ń peléke, ó máa ń fa àrùn ẹ̀dọ̀fóró, ìnira láti mí, ìjayà àti ikú..
wikipedia
yo
Ìwádìí ti fihàn gbangba pé àwọn mìíràn lè ní àrùn yìí láìsí Àmín tàbí ìfarahàn kánkán, nítorí ìdí èyí ni àwọn onímọ̀ ìlera gbà á ní lmọ̀ràn pé ẹnikẹ́ni tí ó bá ti sún mọ́ ẹnití àyẹ̀wò fihàn pé ó ní àrùn náà gbọdọ̀ wá ní imojuto láti ríi dájú pé kó lùgbàdì àrùn náà.Àsìkò ìyàsọ́tọ̀ fún ẹni tí ó bá kó àrùn náà àti ìgbà tí àwọn Àmín rẹ̀ máa bẹ̀rẹ̀ sí ní jáde máa n tó ọjọ́ kan sí mẹ́rìnlá, ọjọ́ márùn-ún lọ ṣáá a máa ń jẹyọ jù..
wikipedia
yo
In one case, it had an culpablebation period of 27 days.Nigba miiran ewe, arun COVID-19 kìí ní àmìn ìfarahàn lara ẹlomiran.Àwọn itọkasikòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn koronaCOVID-19àwọn imọ nipa COVID-19 ti o ṣe pataki..
wikipedia
yo
Ẹranjẹ l' ó jẹ́ fún wọn láti máa ro ìtumọ̀ orúkọ tí wọ́n bá gbọ́ tàbí tí wọ́n bá ń lọ..
wikipedia
yo
Orúkọ, ti eniyan tabi Ọjà tabi Ìlú tabi Àdúgbò bá ń jẹ́, kún fún ìtumọ̀ pataki tí àwọn eniyan máa ń ranti nígbàkúùgbà..
wikipedia
yo
ti iṣẹ̀dalẹ àwọn Yorùbá la n wí yí ọ, kì í ṣe ti ayé d'ayé òyìnbó ti èdè Gẹ̀ẹ́sì n sọ ọpọlọpọ ọmọ Yorùbá di aláìmọ̀kan nípa àṣà àtayébáyé ilẹ̀ wa..
wikipedia
yo
Orúkọ àbísọ ni àwọn orúkọ wọ̀nyí, nípa wọn la sì ń pòwe pé; “Ilẹ̀ l’á á wó k’á tóó s’ọmọ lórúkọ".
wikipedia
yo
Oríṣi orúkọ míràn wà tí Yorùbá ń sọ ọmọ wọn, èyí ni àwọn orúkọ àmútọ̀runwá tó jẹ́ pé ìtumọ̀ wọn dálórí irúfẹ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ọmọ wà nínú oyún tàbí nígbà tọ́mọ náà jáde láti inú ìyá a rẹ̀..
wikipedia
yo
We iwọ mọ́rùn nígbà tí a bíi); Jimọ́ọn (ọmọ tí a bí lọ́jọ́ jímọ́ọn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
wikipedia
yo