cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àsálà ní èso igi èyíkèyí nínú àwọn ẹ̀yà igi tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pè ní Julang . Jẹ́ ọ̀kan lára èso jíjẹ nígbà tí ó bá ti gbó.ànfàní Èso àsálà èso àsálà dára fún wíwo àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dára fún kí ọpọlọ ó pé.Ìrísí rèéṣọ àsálà rí róbótó, epo rẹ̀ dúdú mini, àmọ́ tí a bá fọ̀ tàbí làá, inú rẹ̀ funfun báláú tí ohun kan fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun sì pín èso kan tí a là yí sí ọ̀nà méjì.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àgbò jẹ́ ohun mímu ati ọ̀kan pataki ninu ohun tí a lè fi ṣe ìwòsàn àgọ́ ara nípa kíkọ́ egbògi, ewé, ati epo ìbílẹ̀ pa pọ̀ láti lè fi tọ́jú àìsàn, àrùn ati óorisrisi ohun ti o lè fa ailera si ara ẹ̀dá tabi ẹranko.anfani àgbọ́lara àwọn anfani àgbo ni ó rọrùn lati ri nitori ó wà ní àrọ́wọ́tó wà ní àwọn agbègbè wa gbogbo.
wikipedia
yo
Àgbò ma ń fọ ­ kúrò lára pátá pátá pátá.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Andrew Fielding je omo bibi Ilu citationmp, ni ilu London ni orile-ede England..
wikipedia
yo
A bí nínú oṣù Belu, ó sì kú ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù Èbìbì ọdún 2012..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Onímọ̀ Iwadi oun pẹlu Alan ati John Carew lori imo Oogun..
wikipedia
yo
ìwádí rẹ̀ dalẹ̀ ìmọ̀ iṣan ara àti pàtàkì lórí ìbáṣepọ̀ iṣan nínú ara..
wikipedia
yo
O jẹ Aare fun awon Royal Society lati ọdun 1980 si 1985.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Mahdi Aliyu gusau Igbakeji Gomina lọwọlọwọ ti Ipinle Zamfara ..
wikipedia
yo
O jẹ ọkan ninu Igbakeji alabojuto ti abikẹhin lati dibo ni Ojo-ori rẹ lati ojo kerin ti orile-ede Naijiria ..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ si gbogbogbo Aliyu Mohammed Gusau, Minisita fun Aabo Aabo..
wikipedia
yo
Aliyu Muhammad gusauàwọn itọkasi àwọn ènìyàn alààyẹ̀àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara..
wikipedia
yo
àpótí jẹ́ ohun ìjókòó tí ó ní orí pẹrẹsẹ tí a fi igi tàbí pákó ṣe..
wikipedia
yo
Ẹnìkan ṣoṣo péré ni àpótí lè gbà lórí ìjókòó kan, bákan náà ni kò ní igun tí a lè gbé owó le lọ́tùn tabi lósì..
wikipedia
yo
Ó ma ń ní ẹsẹ̀ méjì, mẹ́ta tàbí mẹ́rin, èyí dá lórí agbègbè tí a bá ti ríi..
wikipedia
yo
A kò lè sọ wípé àga ní àkò, nítorí ai ní apá tàbí igun tí a lè fi ọwọ́, tàbí fi ẹ̀yin ti ṣí..Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ ìṣe ni ọ̀rọ̀ tí ó ń fi ohun tí à ń ṣe lọ́wọ́ tí a ti ṣe kọjá tabi ohun tí a óo má ṣe lọ́jọ́ iwájú hàn ninu gbolohun..
wikipedia
yo
èyí ni kókó inú gbólóhùn èdè Yorùbá, òhun ni ó wà láàrín Olúwa àti àbọ̀, ó lè síwájú Olúwa ó sì lè síwájú ãbò, òpómúléró inú gbólóhùn ni ọ̀rọ̀ íṣe jẹ́.Àwọn ìtọ́kas sí..
wikipedia
yo
Oba Sikiru Kayode Adetona (ti a bi ni ojo kewa osu karun odun 1934) ni Awujale ti Ijebu..
wikipedia
yo
Wọ́n fi jẹ oba ní ọdún 1960, èyí ló mú kí Adetona jẹ́ ọ̀kan lára àwon oba tí ó ti pè lórí alefa ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bàbá re ni omo oba Rufai Adetona ti Iya re si je alaja Wolemotu Ajibioba Adetona (NE Onasile)..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi ọba, ó jẹ́ aṣojú fún ìdílé ọba Anikilaya.Ọba Sikiru Kayode Adetona ti lo ọgọ́ta odun ó lé ọdún méjì lórí àlélélé àwọn bàbá ńlá wọn,ẹ̀kọ́ ọdọmọde omo oba Adetona lọ sí orisirisi ile eko bi i ile-eko ti Onítẹ̀bọmi (Baptist) tí ó wà ní Eroko ní Ijebu Ode; ilé-ẹ̀kọ́ Alakọ́̀kọ́ Ọ̀wé tí ó wà ní òkè-agbo ni Ijebu-Agbo Igbo, àti ilé-ẹ̀kọ́ Ansar-Ud-deen ní Ijebu Ode laarin ọdún 1943 sí ọdún 1950..
wikipedia
yo
Ni itesiwaju lo si ile-eko giga ti koleeji, O lo si koleeji Olu-Iwa (eyi ti o di Adeola Odutola bayi) ti o wa ni Ijebu Ode lati odun 1951 si odun 1956..
wikipedia
yo
Laarin odun 1957 si odun 1958, o se ise pelu ẹka ti o nse ayewo nipa owo ni Ibadan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1958, ọmọ ọba Adetona kọ̀wé fi iṣẹ́ sílẹ̀ láti tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ lórí Olúwáted owó (AccounWW) ní ìlú aláwọ̀ funfun (United Kingdom), ìlú tí ńṣe ìsọ orílè èdè Nàìjíríà nígbà ná.Ipò Ọba látipasẹ̀ lẹ́tà tí wọ́n kọ ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kíní Ọdún 1960, èyí tí akọ̀wé àgbà tí ìjọba ìbílẹ̀ fi ránṣẹ́ sí Olùdámọ̀ràn ìjọba ìbílẹ̀ ti Ìjẹ̀bú ọdẹ pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà Baálẹ̀ Ìgbìmọ̀ fún agbègbè ìwọ̀ Oó fún yín fún Ọba Sikiru ní ọdún àìmọ́ gẹ́gẹ́ bi ọba àti fífi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ bí Awùjalẹ̀ ti ilẹ̀ Ìjẹ̀bú láti ìgbà tí wọ́n ti kọ lẹ́tà yí ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kíní Ọdún 1960..
wikipedia
yo
Eyi lo mu ki awon olokiki omo ile Ijebu bi i oloogbe Ogbeni-Oja, Oloye (Dokita) Timothy Adeola Odutola, Bóbá 1 Oloye Emmanuel Okusanya Okunowo ati Asiwaju, Oloye Samuel Ọlátúbọ̀sún Shonibare se eto ìpadà bọ ọba ti won sese yan wa sile..
wikipedia
yo
Ni ojo kejidinlogun osu kini odun 1960, olori igbimo afobaje ti ile Ijebu, Ogbeni-Oja, Oloye Timothy Adeola Odutola se afihan oba tuntun fun gbogbo agbaye..
wikipedia
yo
Àfihàn yí ni ó jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ayẹyẹ fífi ọba tí wọ́n bá ti yàn sí orí ìtẹ́..
wikipedia
yo
Lehin eyi ni oba ti won yan yi yio tesiwaju lo si Ioba ni "Odo" fun osu meta.Ọba Sikiru Kayode Adetona, eni ti "ODIS" ti NU yan pelu awon marun miran ni awon afobaje pana mu ni ibamu pelu abala ikokanla ofin oye jije ti odun 1957 ni agbegbe iwo Oorun ile Naijiria..
wikipedia
yo
Gomina nigba na fi owo si yiyan Sikiru Kayode Adetona gege bi Awujale ti ile Ijebu..
wikipedia
yo
Ayeye ìgbadé waye ni ojo Àbámẹ́ta ti i se ojo keji, osu kerin odun 1960.Ni ojo iṣẹgun ti i se ojo karun osu kerin odun 1960, oba tuntun, oba Adetona darapo mo awon oba ti agbegbe iwo Oorun lehin ti won ti se afihan re..
wikipedia
yo
Èyí ló mú kí àwọn ọba àti àwọn ìjòyè dárúkọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ fún ìgbìmọ̀ lọba lọba..
wikipedia
yo
Sugbon eni ti o ti dagba ti o si tun je agba oba gege bi isedale, oloogbe sir Adesoji Aderemi, Ooni ti Ile-Ife ni won pada wa yan gege bi i aare..
wikipedia
yo
Èròǹgbà wọn ni pé gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́mọdé ọba, Awùjalẹ̀ tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún yíò ní akitiyan fún ipò gíga yí..
wikipedia
yo
La i se aniani, erongba yi lo mu ki won gba Awujale ti ile Ijebu gege bi eni oto.Awon itọkasi awon oba ati ijoye ni Naijirimeje eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1934..
wikipedia
yo
Ìgbà tá a kú là á rẹ̀sẹ̀ ,ènìyàn kò sunwọ̀n láàyè,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ọ̀rọ̀ ìsìnkú ní ilẹ̀ Káàárọ̀ ó ò jíire.Adìyẹ ṣe pàtàkì nínú ètò ìsìnkú àgbà...
wikipedia
yo
Èrè ọmọdé gbogbo ọmọdé ní orílẹ̀-ayé ni ó fẹ́ràn eré ṣíṣe nínú ilé,nínú ọgbà, ní àdúgbò àti ní ìgbel..
wikipedia
yo
Ọmọde a máa bá gbogbo eniyan ṣiré tabi kí ó jáde láti bá ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ ṣiré ní àdúgbò kan náà..
wikipedia
yo
Inú dídùn àti ẹ̀rín jẹ́ àmì eré ṣíṣe láàrín ọmọdé àti àgbà..
wikipedia
yo
Akọ́mọlédè Ìjìnlẹ̀ Yorùbá Vol 1oríṣiríṣi eré Ọmọdéàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abi arabinrin "Efunporoye OsunTinubu Olùmọsa" ni odun ìró..
wikipedia
yo
O jẹ eni ti o gbajumo ni ilu Eko nigbati oba Adeniji adelé , Oluwole, akíntóyè ati Dosumu wa lori oye nigba naa..
wikipedia
yo
Àbí akínkanjú obìnrin yìí ní agbègbè ọjọ́koro ní ìlú Ẹ̀gbá tí orúkọ bàbá rẹ̀ á sì máa jẹ́ Olùmòṣà..
wikipedia
yo
Òkò akọkọ rẹ wá láti ìlú owú tí o sì bí ọmọ meji fun..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí arákùnrin yí papòdà, ó fẹ́ ọba adelé Adépù ní ọdún 1933 nígbàtí Tinúbú bẹ Ìlú Abeokuta wo tí a sì fi ogun fẹ́..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀lé ọba yìí dé ìlú Badagry tí ó jẹ́ ibi ìfarapamọ́ sí fún àwọn ọba Àlàyé nígbà náà.Nàìjíríà ní ìlú Badagry yìí Bákan ná à, ó lọ ipò ìyàwó ọba tí ó wá láti ta àwọn ọjà tí ó lòdì sí èyí tí ó yẹ kí ó tà bíi Tobakọ́, iyọ̀ àti ọwọ́ ẹrú.Ìyá ọba ní ọba ọba àti ajẹ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹfunroye parí ìjà Efunroye síi kúrò ìlú..
wikipedia
yo
Sjia gambo sáwabá tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kejì ọdún 1933, tí ó sìn ṣaláìsí lóṣù Kẹwàá ọdún 2001 (15 February 1933– October 2001) jẹ́ ajìjàǹgbara ètò obìnrin, àfọwọ́ṣàánú àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òun ni igbákejì alága ẹgbẹ́ òṣèlú Great Nigeria People's Party, tí wọ́n sìn tún yàn án gẹ́gẹ́ bí olórí àwọn obìnrin nínú ẹgbẹ́ Northern Element Progressive Union (Nepù).Aáyán gẹ́gẹ́ bí òṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ènìyànláti ọmọ ọdún méjìdínlógún ní sáwabá ti bẹ̀rẹ̀ òṣèlú..
wikipedia
yo
Lásìkò náà, ẹgbẹ́ òṣèlú Northern People’s Congress ni ó gbajúmọ̀ jùlọ lápá àríwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí àwọn ọba wọn pẹ̀lú àwọn aláṣẹ ìjọba àmúmisìn láti orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì ń gbè wọ́n lẹ́yìn nígbà náà, ṣùgbọ́n ní tirẹ̀, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò, Northern Element Progressive Union (Nene)..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùpolongo tako gbígbé ọ̀dọ́mọbìnrin màjèsín ni ìyàwó, iṣẹ́-ipá àti àṣegbé ẹ̀kọ́ kíkà lápá àríwá Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Gambo, bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ nígbà tí ó bọ́ síta pẹ̀lú ìgboyà níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ òṣèlú kan tí ó sìn sọ̀rọ̀ níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà tí ó kún fún ọkùnrin ṣoṣo..
wikipedia
yo
Arabinrin Funmilayo Ransome-Kuti ni o tọ ọ sọ́nà nigba naa, ti o sin wá sọ́dọ̀ rẹ ni ìlú Abeokuta lẹ́yìn ìgbà náà..
wikipedia
yo
Oun obinrin akọkọ ti o bẹrẹ ijàǹgbara awọn obinrin apa Ariwa Naijiria.Awon itọkasiàwọn oloselu ará Naijiria..
wikipedia
yo
Judith Susan Sheindlin ( née Blum; ni abi ni ojo kokanlelogun osu kewaa, odun 1942..
wikipedia
yo
Sheindlin ti gba ami-ẹ̀yẹ ìdáni lọlọ́lá ti Day-time Emmy Award ní ọdún 1996.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ènìyàn aláàyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1942àwọn ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Aṣọ àdirẹ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn aṣọ ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Tọmọdé tàgbà ni ó ń wọ aṣọ àdirẹ ti wọ́n ṣiṣẹ́ ọnà Orissarisi si lára nílànà ìbílẹ̀, ti ó si wà ni àwọ̀ Orisirisi si.Àwọn Ìtọ́kasí Yorùbá..
wikipedia
yo
Hilda Dokubo tí a tún mọ̀ sí Hilda Dokubo MRakro jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn ọ̀dọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti fìgbà kan jẹ́ olùgbaninímọ̀ràn pataki lori ọ̀rọ̀ ọ̀dọ́ fun gómìnà àná ìpínlẹ̀ Rivers, Peter Odili.Igba Ewe ati aáyan Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹwọn bi ni Hilda Dokubo, ti o jẹ́ àkọ́bí fun awon obi re ilu Buguma, ni asa-tòru, Ipinle Rivers, nibi ti o ti kawe akobere ati sekondiri ni ile iwe St Mary State School, Dupo AgGrey ati government girls Secondary School..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìẹ̀jẹ́ ẹ̀rí dìgírì àkọ́kọ́ àti ìkejì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ tíáta ní onílà.Iṣẹ́ Òjẹ́ ìṣèkòrí, iṣẹ́ Agùnbánirọ̀ ní Dokubo kópa nínu sinimá àgbéléwò àkọ́kọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Evil Passion lọ́dún 1992..
wikipedia
yo
Láti ìgbà náà ló ti di gbájúmọ́ òṣèré ìlúmọ̀ọ́ká nínu sinimá àgbéléwò, tí ó sin tí ṣe olóòtú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò lédè gẹ̀ẹ́sì àti Ìgbò..
wikipedia
yo
Emeka ikeje gbajumọ osere ọmọ bibi orile ede Naijiria.Àtòjọ Àwọn sinimá àgbéléwò Reafter my Hearttest My heartstrength of a womana can of Worms Affairstistisóríbúrẹ́dì Loesecuret Acthouse and the manthe snake girlmy last weddinggu battlewind of Love100 Days in the JunNot Man Enoughfegbòde Dayríykáwọn itọkasiàwọn oṣere ara Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ ọtí lile ibilẹ ti wọn pọn lati ará ẹmu igi ọ̀pẹ tàbi agbè..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọtí lílé ìbílẹ̀ tí wọ́n máa ń mu káàkiri ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà, pàápàá jùlọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Lóde òní, ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń ka Ethanol sí ògógóró, ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ rárá..
wikipedia
yo
Kẹ́míkà ni Ethanol, ṣùgbọ́n ògógóró jẹ́ ọtí lílé ìbílẹ̀ tí wọ́n pọ́n láti ara ẹmu igi ọ̀pẹ tàbí agbe.Àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n ń pe ògógóróakpẹ̀tẹ̀shie lórílẹ̀ èdè Ghana, omi Sapele, Paraga, Ojúd-ewú, sùn gbalaja, eégún inú ìgò, jẹ́ díẹ̀ lára àwọn onírúurú orúkọ tí àwọn ènìyàn máa ń pe ògógóró káàkiri ilẹ̀ Yorùbá àti Áfíríkà..
wikipedia
yo
Àwọn orúkọ mìíràn tí onírúurú àwọn ènìyàn tún máa ń pè é ní Ufọ́fọ́p ní Calabar, rọ̀bìrọ̀bì ní Abeokuta, baba erin Iléṣà, òyìnbó Go, Cordaradún, ètòńtọ̀ lédè àdàmọ̀dì Gẹ̀ẹ́sì, wùrù, àwọn Ijaw, údìgan Ọ̀rugàn àti Bìní, àgbàgbà Urhobo,àti bẹ́ẹ̀àti bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
names in red do not have a page in the Yoruba Wikipedia.Each of these women has a page in the English-language Wikipedia..
wikipedia
yo
They are found in that Category, and can be used as a base to translate to Yoruba.other names can be added below..
wikipedia
yo
Òkè Olùmò níoke kan tí no wà ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òkè olùmọ̀ jẹ́ ibisálà fún àwọn ará Abeokuta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí wọ́n sì ń bòó pẹ̀lú Orissarisi ẹbọ.Àbẹ̀wò sí Òkè OlúmọÒkè Olúmọ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn òkè gbajúmọ̀ ti àwọn ènìyàn ma ń lo bẹ̀wò láti gbafẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíìpínlẹ̀ Ogunjẹografi ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jorinia Kehinde fatunsin je awalẹ̀pìtàn omo Naijiria, eyi ti awon onimo Geesi mo si archaeologist..
wikipedia
yo
Wọ́n kà á sí obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìṣẹ̀ǹbáyé ní Nàìjíríà, àti obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ olórí ilẹ̀ ṣèrànwọ́ orílẹ̀-èdè Ìbàdàn (National Museum of Ìbàdàn).Iṣẹ́ iṣẹ́ ààyè rẹ̀ ti dojúkọ púpọ̀ jùlọ lórí àmọ́ mímọ́ Yorùbá, pàápàá láti agbègbè owó.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí wulẹ̀wulẹ̀ ti àwọn Òwuléwutantún bẹ̀rẹ̀ wulẹ̀ wulẹ̀ nínú ilẹ̀ ìlú Igbója àti Ìjẹ̀bú-owó láti ṣàwárí ohun àlùmọ́nì tí wọ́n ń pè ní [ Terracotta] lọ́dún 1981..
wikipedia
yo
Ogbeni Babasẹhinde Ademuleya lati ifáfitì Obafemi Awolowo University ṣakiyesi pe ayewo re ni igba keji ti ise iwadii wúléwúlé bayii waye leyin ti ekpo Eyo ti o waye lodun 1976..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ wù kí ó rí, ìwádìí Fátúnsìn ni ó ṣàlàyé orígúrun lórí àwọn eré.Iṣẹ́ rẹ̀ lórí àwọn kíkọ̀ fàtúnsìn tí kò nípa ipa tí wulẹ̀wulẹ̀ ti àwọn òwúléwu ní àwọn Museum Nàìjíríà àti ipa rẹ̀ lórí àwọn ohun-ìní àṣà ní orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
A ti mọ ọ gẹ́gẹ́ bí aṣáájú-ọ̀nà fún ìrònú àti ìtumọ̀ wulẹ̀wulẹ̀ ti àwọn òwúléwutan lẹhin òmìnira ni ilẹ̀ Afirika.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nicole Scherkan ( /S E:R Z í n əd / ; bi Nicole Prescovia EliKolani Validepo; June 29, 1978) jẹ́ akọrin, onijo, òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti gbajúmọ̀ olóòtú Church ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàigba Ewe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀wọ́n bi i ní ìlú Honolulu, ní Ìpínlẹ̀ Hawaii, ó gbé Louisville, Kentucky dàgbà, ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ti Wright ṣááju kí ó tó jáde sílẹ̀ láti lépa ìrìn-ajo orin kan pẹ̀lú ẹgbẹ́ apata Ilu Amẹ́ríkà tí Oran Days of the New nípasẹ̀ Popstars..
wikipedia
yo
Scher: Dide di olokiki bi akọrin olorin ti awon ọmọlangidi pussy ati tu awọn awo orin pCD (2005) ati Doll Domination (2008) di ọkan ninu awon egbe ọmọbirin ti o dara julo ti gbogbo agbaye ni gbogbo akoko.Awon itọkasi awọn eniyan alààyẹ̀awon Ọjọ́ìbí ni 1978awon akọrin ara AmeriKaal/18 with Hcards..
wikipedia
yo
àbísọye Ajayi AkinFolarin tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkàn Oṣù Kàrún ún, Ọdún 1985 (19 May 1985) ní Ìpínlẹ̀ Òndó jẹ́ oníṣẹ́ àdáni àti Olú polongo ìkẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ìyá tí kò ní ànfàní láti kẹ́kọ̀ọ́..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ àjò 'Pearls Africa Youth Foundation', tí kìí ṣe ti ìjọba tí ó sì ń lo àjò náà láti kọ́ àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ìyá nípa ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
Wọ́n fún AkinFolarin ní àmì-ẹ̀yẹ akọni CNN (CNN Heroes) ti ọdún 2018 ní ọjọ́ Kínní Oṣù kọkànlá, Ọdún 2018, nígbà tí wọ́n tún fi orúkọ rẹ̀ sínú àwọn obìnrin ojú àkọ́kọ́ ti BBC (100 Women (BBC) *Women) ní òpin Oṣù yí kan náà.Iṣẹ́ rẹ̀ Ajayi AkinFolarin bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ ẹ̀..
wikipedia
yo
Níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ fún odidi ọdún méje gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ṣe, ṣáájú kí ó tó ṣiṣẹ́ dé ipò associate aláràbarà ní ilé iṣẹ́ náà..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ, SkinFolarin ṣàkíyèsí wípé iye àwọn obìnrin tí ó nímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ kò tó nkan, pàá pàá jùlọ bi iwadi ti Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe ni ọdún 2013 ni àgbọ̀nrín yí fi han wípé ìdá mẹ́jọ péré nínú ìdá ọgọrun un àwọn obìnrin ló nímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Èyí ni ó gun Ajayi ní fẹ́ràn láti dá àjọ tirẹ̀ kalẹ̀ tí yóó ma Samojuto aléà yí.ní ọdún 2012, Ajayi dá Pearls Africa Youth Foundation' kalẹ̀ láti lè mú ìdàgbà bá àwọn obìnrin nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ..
wikipedia
yo
tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kẹwàá ọdún 1980 (13th October 1980) jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ti kópa lórísisí àwọn àwọn sinimá-àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n ipa tó kó nínu sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ n "The Last Three dígíts lọ́dún 2015 ló sọ ọ́ di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́ká.àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Muhammadu Sanusi II tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sanusi lámì Sanusi tí wọ́n bí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù Keje Ọdún 1961 (31 July 1961) jẹ́ Emir ana tí ìlú Kano tí ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano lábẹ́ ìṣàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Gandu Rodu lọ́yẹ̀ lọ́jọ́ kẹ̀sán-án Oṣù Kẹta Ọdún 2020..
wikipedia
yo
Láó yìí kan náà ní ìjọba ìpínlẹ̀ Kano kéde Aminú Adó alábáro gẹ́gẹ́ bí I Emir tuntun fún ìlú Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 2014 lámì Sanusi ló gori ìgbe ìyé àwọn onímọ̀ rẹ̀, lẹ́yìn ikú Ọba Emir ìjẹta, Adowo láaye.kí ó tó jọba, Sanusi jẹ́ ogbontarigi onímọ̀ nípa okoowo àti gomina ilé ìfowópamò-àgbà ti Nàìjíríà lati ọdún 2009 sí 2014, tí ààrẹ, Goodluck Jonathan pàè kí ó dá dúró látàrí owó kan tí Sanusi láẹ̀ pé ó sọnù ní ó lọ-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ó ń ṣe pẹ̀lú òyé epo epo lẹ̀, N Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abdullahi Umar Gandu, OFR tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1945 (25 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015..
wikipedia
yo
Kí ó tó di Gómìnà, òun ni igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, LỌ́DÚN 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano..
wikipedia
yo
Ìgbéyàwó Ìṣẹ̀ǹbáyé ni wọ́n ń pè ní "Ìgbá Ukwu" ní ilẹ̀ ògbò..
wikipedia
yo
Ni apá ila oorun ile Naijiria, igbeyawo kii ṣe isọsọ láàarín ọdọọdọ ati Ọdọmọkunrin to fẹ di ọkọ ati aya nikan ṣugbọn ojuse awọn obi, awọn ẹbi ati awọn ara adugbo..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí ìkọ̀sílẹ̀ fi ṣọ̀wọ́n láàárín wọn.Lẹ́yìn tí ọkunrin bá ti rí obinrin tí yóo fi ṣe aya, ohun àkọ́kọ́ tí yóo ṣe ni pé kí ó fi tó àwọn òbí rẹ̀ létí..
wikipedia
yo
Ẹ̀tọ́ Mọ́mì-n-mọ̀-ẹ́ ní oríṣìíríṣìí ìgbésẹ̀ ninu igbeyawo igbó.Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ninu ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ yìí ni ọkunrin tí yóo fẹ́ iyawo yóo ti lọ yọjú sí baba iyawo tabi ẹbí rẹ̀ (iyawo) kan, baba rẹ̀ ni yóo sìn-ín lọ..
wikipedia
yo
Ní àkókò fífi ojú gan-an-ni baba iyawo yìí, tí ó sábà máa ń wáyé ní ìrọ̀lẹ́, baba ọkọ yóo sọ ìdí tí wọ́n fi wá rí wọn..
wikipedia
yo
Àwọn òbí ìyàwó yoo gbà wọ́n tọwọ́tẹsẹ̀ ṣùgbọ́n wọn kò ní fún wọn ní ìhùn pàtó sí ohun tí wọ́n bá wá.Ìgbésẹ̀ Kejì̀ nírúkọ ìkòkòkòpò..
wikipedia
yo
of in ètò ẹ̀kọ́ èdè abínibí ló fa ẹ̀kọ́ èdè àkọ́kúntẹni..
wikipedia
yo
Èdè àkọ́kúntẹni ni kí a kọ́ èdè mìíràn tí kì í ṣe ti àwùjọ tí a bí ní sí kùn èyí tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo