cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ olóòtú lórí ètò lórí rédíò láti ọdún 2005.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sin tí yàn án fún àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrébìnrin tí ó dára jù ní ipò amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Olú-ẹ̀dà Ìtàn Lọ́dún 2009 àti 2011.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ará Nàìjíríààwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàn Oṣù Kẹwàá ọdún 1988 (21st October 1988) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, ọmọba Jide Kosoko.. | wikipedia | yo |
Ẹbí wọn ni a bá má pè ní ẹbí sinimá àgbéléwò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, nítorí yàtọ̀ sí bàbá rẹ̀, ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Sola Kosoko àti ìyàwó bàbá rẹ̀, olóògbé Henrietta Kosoko náà jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ara Naijiribọ̀wọ̀ ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
jẹ́ ọdọmọbinrin ọmọ ọdún mẹrinlelogun tí ó jọba nípò adelé ní ìlú ààyè ní ìpínlẹ̀ Òndó lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó wà lọ́mọ ọdún méjìlélógún, ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifáfitì, Achievers University, ní ìlú Ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, tí ó ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣẹ́gun Òyìnbó lọ́dún 2017 tí ifá fi yàn án lẹ́yìn tí baba rẹ̀, tí ó jẹ́ ọba, Kábíyèsí alààyè ti ìlú ààyè, ọba J.. | wikipedia | yo |
Taiwo OyeBola Agbona ni o wa nipo oba ilu aaye, gege bi adele, ti o sin n pase ilu naa lọwọlọwọ.Awon itọkasiawon ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Achievers University jẹ́ ilẹ̀ ẹ̀kọ́ gíga Ifáfitì tí wọ́n tẹ̀dó sí ìlú Ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó , lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ó jẹ́ Ifáfitì aládàáni tí wọ́n dá sílẹ̀ lọ́dún 2017, tí ìjọba àpapọ̀ sìn fọwọ́ sí.. | wikipedia | yo |
ifáfitì Achievers University jẹ́ ọ̀kan lára ilé iṣẹ́ Èkó, The Achievers Group of Education and Training Organization, tí ó gúnwà sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ọ̀gbẹ́ni bodè ayọ̀rìnde àti àwọn onímọ̀ nípa ìkẹ́kọ̀ọ́ mìíràn ni wọ́n dá a sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àjọ tí ó n ṣe kòkárí ètò ẹ̀kọ́ Ifáfitì lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà The Nigerian National University Commission kà á sí ipò mẹ́tàléláàádọ́ta nínú àwọn ifáfitì tó pọ̀jùwọ́n lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2013.Àwọn ìtọ́kasíYunifásítì ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ìdásílẹ̀ lẹ́yẹ̀wò ti National University Commission, (NUC) ti ìjọba àpapọ̀ fún láṣẹ lọ́lẹ̀-èdè Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
Achievers University, Owo , Ìpínlẹ̀ Oǹdó Jáv University, Èdè daṣọ, Osun Admiral University, Ìbúsa G State, Aroko G-Ekiti ipinle Ekiti, ipinle African African University of Science & Technology, Abuja Alagi, Technology G, Ipinle Oyo, Fun Al-hi Mehi University, E-H B- -Q, F-Q American University, May ipinle Didewa, ipinle Alato anchor Mi anchor ipinle 2020 Jayele 2018 September So[4] Akka University, Maika, Oyo Augustine Augustine Augustine, Oroko University, ìliṣàn - ipinle Ogun- Oroko, ipinle University Mels, Oroko University Me ọta Ogun Ogun Ogun Ogun Saway, Ipinle Mi 2016, Ipinle University, Taiwo Me Me Olutiwa, Ana Mi Bowen Osun Osun Ore, Yoruba Osun, ipinle Mahi Meobi, Eroko Ere E 20, Isa University, I- 2016, Isa O tun Eko, ipinle York Yàrá Bàbà Es Mi Enugu State, Enugu University, Ipinle Ogun Ogun Ogun Cra O Oja Ogun Ogun Mi Mi O University - Oroko 20 Mi Mi film University, 20 & Mo Èkó, Kai University of Medical & Health & Iroko & Iroko University, I G University, A Ana Ana To Anagbo FM 2015, Iku University, E-Nike O gi ******& Uru Mi Mi Mi Oroko, Ògùn O To O-E O Di Igi Mi University Tuntun Tuntun *****-ara M * * ***- Oja O Osun Mo L FM L Ibadan, O L rara L | wikipedia | yo |
ifáfitì ìjọba pín sí ọ̀nà méjì gbòógì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ijoba apapo ati ijoba ipinle ni won ni eto ati ase lati owo National University Commission, ajo ijoba apapo ti o n dari, mojuto idasile ifáfitì lórílẹ̀-ede Naijiria, lati se idasile ifáfitì.Àtòjọ awon Yunifasiti Ijoba apapo lórílẹ̀-ede Naijiria Abubakar Tafawa Balewa University, Bauch Ahmadu Bello University, Zaria alamọro University, Kano Federal University Gashua Federal University of Petroleum Resources Federal University of Technology, Àkúrẹ́ Federal University of Technology, Minna Federal University of Technology, Owerri Federal University, Dutse, Jigawa State Federal University, Duthoki-Ma, Kat Federal University, Kshe , Gombe State Federal University, Lafia, Násáráwá, Násárál State University, Lokọja, Koraya State Federal University, Ndu- Fọdu, Ebon State University, Oroko, Gailata Federal University, Oye-Ekiti, Ọta State Federal University, Waila University, Taraba State Federal University, Birbi Kebbi University, Birsau University, from Okpara University of Agriculture, Uroko Mo Addo University of Technology, Lé National Osan National University, Nigeria of Nigeria, Lagos University, Lagos University, Eti University, Sata National University, Mo tun *irin Tuntun, Irin ( M | wikipedia | yo |
Nigerian defence Academy, Kaduna Nnamdi Azikiwe University, Awka Obafemi Awolowo University, Ile-Ife The Police Academy Wibùsùn University of Abuja, Gàkàràwalàdá University of Agriculture, Abeokuta University of Agriculture, wón University of Benin University of Calabar University of Ibadan University of Ìlọrin University of jo's University of Lagos University of Maiduguri University of Nigeria, Nsukka University of Port-Harcourt of Port of Uyo of Uyo Danfo Danfowe Universit Awọn Yunifásítì Ijọba Ijọba Ipinle-Èdè Nàìjíríà ] Usódì University, Uturuy. | wikipedia | yo |
Adamawa state University mubi Adekunle Ajasin University, Akun. | wikipedia | yo |
Akwa Ibom State University of Technology, Uyo Ambrose Alli University, Ekpoma, Anambra State University of Science & Technology, uli Bauchi state University, Gadau Benue state University, wíwó. | wikipedia | yo |
Cross River State University of Science &Technology, Calabar Delta State University ábráka ẹbọnyí State University, Abakaliki Ekiti State University Enugu State University of Science and Technology, Enugu Gombe State University, Gombe Ibrahim Badamasi Babangida University, lápái Ignatius Àjùru University of Education, CodénúHananiẹni. | wikipedia | yo |
Imo state University, Owerri Kaduna State University, Kaduna Kano University of Science & Technology, Wìbáwí Kebbi State University, Kebbi kogi State University Valgba Kwara State University, Ìlọrin Ladoke Akintola of Technology, Ògbómọ̀sọ́, Ògbómọ̀sọ́ State University Ojo, Lagos. | wikipedia | yo |
Nasarawa state University, Keffi Niger Delta University, yẹ̀nà Northwest University, Kano Olabisi Onabanjo University Ago-ìwòye Ondo state University of Science & Technology, Okitipupa Osun state University, Oshogbo Plateau State University, Junko Rivers state University of Science & Technology Sokoto state University, Sokoto táì Solarin Univ.. | wikipedia | yo |
of education, Ijebu-Ode Taraba State University, Ìyàwó Technical University, Ibadan Umaru Musa Yar'Adua University , Katsínáàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ikọ́ jẹ́ ọ̀nà gbígbẹ́ àtẹ̀gùn jáde pẹ̀lú agbára láti ọ̀nà ọ̀fun kí a lè fọ ọ̀nà ọ̀fun náà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìdọ̀tí tí ó sá pamọ́ síbẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ikọ̀ wíwú lè jẹ́ lẹ́ẹ̀kan tàbí léra-léra tí yóò sì mú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ dání.Kògùn léra-léra lè túmọ̀ sí wípé àìsàn tàbí àrùn kan wà ní àgọ́ ara nítorí wípé púpọ̀ lára àwọn àrùn àgọ́ ara ni a lè tàn kálẹ̀ tàbí pín fún ọṣíṣẹ́ṣíṣẹ́ ìtọ́jú ìkóṣíṣe ìtọ́jú ìkó pọ̀se pẹ̀lú wíwádi ohun tí ó fa ìkọ́ fúnra rẹ̀, bí a bá ti mọ̀ọ́n, Ìtọ́jú rẹ yóò yá kankan.Àwọn ìtọ́kasíìlera.. | wikipedia | yo |
Ìwé ìrìnà ní àkójọ pọ̀ ìwé ìdánimọ̀ ti ìjọba orílẹ̀-èdè kan sì fi òǹtẹ̀ lù fún ìrìn-àjò ọmọ orílẹ̀-èdè bẹ́ẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun tí ó ṣe kókó jùlọ ni orúkọ ẹni tí ó ni ìwé ìrìnà náà, ibi tí wọ́n ti bíi, ọjọ́ ìbí, àwòrán ìdánimọ̀ pẹlẹbẹ, ìbuwọ́lù ati àwọn nkan tí a lè fi dá ẹni tí ó ni ìwé ìrìnà náà.. | wikipedia | yo |
Pupọ ninu àwọn orílẹ̀-èdè ni wọ́n ti gùn lé ìpèsè Ìwé ìrìnà Onítẹ̀ẹ́lọ́rùn tí ó ní àmì ìdánimọ̀ Chip nínú, tí yóò dènà ṣíṣe ayédèrú ìwé ìrìnà lọ sí ìlú mìíràn..Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìlà Kíkọ Nílẹ̀ Yorùbá jẹ́ kíkọ́ tàbí fífa ìlà sí ojú, orí, apá tàbí ìtàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan pàtàkì tí àwọn Yorùbá ń gbà láti ṣe oṣó, dá ara wọn mọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ bí àṣà àti ìṣe.Ìwúlò ilákòkò ilà kíkọ nílẹ̀ Yorùbá ni kí wọ́n lè mọ ènìyàn mọ́ ìdílé rẹ̀ ní gbogbo ibi tí ó bá lọ.. | wikipedia | yo |
Ìlà yí lẹ jẹ́ ti ìdílé ìyá tàbí ti bàbá àmọ́ lọ́pọ̀ ìgbà, tí ìdílé bàbá ni wọ́n sábà bá ń kọ́ fún ọmọ.. | wikipedia | yo |
Lára ìwúlò ilá tún ni láti fi ṣe oṣó tàbí ṣe ara lóge àti lọ́jọ́.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún máa ń lo ilá láti fi so èmi ẹ̀mí ọmọ Àbíkú ró ki ó má bá kú tàbí padà sọ́dọ̀ àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ mọ́.. | wikipedia | yo |
Bí ó bá tilẹ̀ gbìyànjú láti padà, tàbí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ wá mú tipá-tipá ìlà yí ni yóò jẹ́ kí wọ́n kọ́ọ sílẹ̀, nítorí ilà náà yóò dúró gẹ́gẹ́ bí àmì tí yóò jẹ́ kí irúfẹ́ ọmọ náà ó yàtọ̀.Àwọn orílẹ̀-èdè ti ìlà kíkọ ti wọ́pọ̀àṣà ìlà kíkọ wọ́pọ̀ láàrin àwọn ènìyàn Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà orílẹ̀-èdè Benin, orílẹ̀-èdè Togo.Oríṣi ìlàpẹ̀lẹ́ ìlà pẹ̀lẹ́ ni ìlà mẹ́ta-mẹ́ta sórí èké kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Pẹ̀lẹ́ pé oríṣi mẹ́ta, àwọn ni ; pẹ̀lẹ́ ìfẹ́, èyí wọ́pọ̀ láàárín àwọn ará Ilé-Ifẹ̀.. | wikipedia | yo |
Gbogbo rẹ̀ pátá ló rí bákan náà.Òwu Òwu ní ìlà mẹ́fà lórí èké kọ̀ọ̀kan, tó sì wọ́pọ̀ láàárín àwọn ará Òwu, tó jẹ́ ọ̀kan lára ìlú tó gbajúmọ̀ ní Abeokuta, ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
Oloye Olusegun Obasanjoko ila ilayẹ Ounũ ila Gọ̀se ni a tun mọ si kẹkẹ.. | wikipedia | yo |
Kèké ní ilà bíi ọ̀kan àti ilà tó wò tí wọ́n kọ sí èké kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Àwọn ará Ògbómọ̀sọ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni ó sáábà maa ń kọ ilá yìí.com àbàjà maa ń jẹ́ ìlà mejila, mẹ́fà lọ maa ń wà ní abẹ́ kọ̀kọ̀.. | wikipedia | yo |
Òun sì ni ọba làdi Adéyẹmí III, tó fìgbà kan jẹ́ Aláàfin Ìlú Oyo Àwọn Ìlà Mìíràn Ta Ní Ní Èdè Yorùbá ní ture, nílẹ̀mẹyà, bámú àti Jamgbàdí.Orúkọ àwọn èèyàn ìlú-ọn-ká-ka tí wọ́n Kọ́lá Ladoke Akintola Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ Lamidi Adéyẹmí III Ayọ̀ Ladigbolu Ayọ̀ Fobase Adegboyega Dosunmu II II Christopher Àlàó-àkàlà Salihu Modibo Alfa Belú King Sunny Adery Brymo Ọlániyi Atẹ̀dówọ́n Ìtọ́kasí Wo orisun.. | wikipedia | yo |
Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tí a le ṣe ìkékúrú rẹ̀ sí (tsp) jẹ́ ilé iṣẹ́ tí ó eà ní ọ̀nà bí a ṣe le rí ara ẹni bá sọ̀rọ̀, yálà nípa lílo ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́, tàbí ìtàkùn ayélujára.. | wikipedia | yo |
Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni ṣòro tàbí T£ps, ni o jẹ́ wípé nígbà kan rí, ìjọba orílẹ̀-èdè nìkan ló ma ń ṣàkóso lórí pípèsè irúfẹ́ ohun èlò ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ nítorí owó tabua tí o ma ń náni láti pèsè rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àmọ́ nkan ti yí padà ti àwọn ilé-iṣẹ́ aládàáni náà ti ń pèsè àwọn ohun elo yi.Awon ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìlà ìpè ni a lè pè ní àmì ìdánimọ̀ fún oníbàárà (Subscriber identity Module) tí gbogbo ènìyàn ń pè ní SIM Card, jẹ́ Amupamọ́ Circuit) kan tí ó wà fún títọ́jú orúkọ àti àwọn àmì ìdánimọ̀ gbogbo tí oníbàárà bá fi sílẹ̀ lásìkò tí ó fẹ́ gba ìlà ìpè rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun tí oníbàárà fi sílẹ̀ yí ni yóò jẹ́ ohun tí wọ́n lè fi ṣe ìdámọ̀ rẹ̀ lórí ìtàkùn tàbí lórí ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́.. | wikipedia | yo |
O se e se ki a fi orukọ ati ila ipe awon eniyan bi ebi, ọrẹ ati bee bee lo pamo sori ila ipe wa.Ibi ti a ti le lo ila ipea le lo ila ipe ni ori ero ilewo, satati,, agogo ọrun owo, ero Kọmputa tabi awon ero ayaworan ti onikaapa iru re.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Bright Chimezie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní Oṣù Kẹwàá Ọdún 1960 (1st October 1960) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ìgbà kan ọmọ bíbí Ìgbò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Monalisa oṣó tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kesàn-an Ọdún 1974 (13th September 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ olóòtú ètò orí ìlú àti gbajúmọ̀ olugbohunsafefe.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Jiopolima (Ggbọ́rọ̀ramers) Jiopo je ohun elo atọwọda, gege bi SeraMiki, awon ohun ti ogun, ti o sopọ pelu Covalent, awon Netiki ti koni gantan (Aphous).. | wikipedia | yo |
Àjẹkù obdian (gílásì dídáàrùnti) jẹ́ pati díẹ̀ nínú àwọn ohun èlò fún jíopogbádùn .. | wikipedia | yo |
Awon Polima le je ohun elo adayeba, bi nkan orisun-carbon, tabi atọwọda Polima, fun apẹẹrẹ - lati orisun ohun àlúmọ́nì (Contra).. | wikipedia | yo |
Awọn Polima adayeba ni oriṣi kilasi bi adámọ Polima (Natural, cellulose), awọn àdàmọ̀dì adayeba Polima (bi okun aṣọ, Ike, Awon fiimu, Awon nkan ti Ama ran, ati bẹẹbẹ lo) ati Polima abinibi (isedale, oogun, ile elegbogi).. | wikipedia | yo |
Joseph Davidovits jẹ eniti o fun ni oruko yi ni ọdun 1978 ti o si se àdásilẹ ajo imo-ijinle Faranse (Association Loi 1901) Institut GUattamere (Ile-ẹkọ JiopoUnbUn). T.f.. | wikipedia | yo |
JiopoAlakoso je pataki ohun elo kemikali àlúbo fun apẹẹrẹ Inw-oxide (--O-O-SI.. Intueco- teminate In-O-O- ferro- Al-minate (-fe-O-O-O-O--) tabi alurSh-Qgbo (-al-O-O-dúdú ti a ṣẹda nipasẹ ilana ti GUzmerization | wikipedia | yo |
iṣelọpọ nkan tí ó wà ní erùpẹ̀ ilẹ̀ yìí (GEOsynthesis) ni a gbékalẹ̀ àkọ́kọ́ ní àpéjọ ìùc ní ọdún 1976.. | wikipedia | yo |
Alaye fun ọna to dale ti ipilẹ Àìsídi wa ni.kini JiPolima? Ni bii ọdun 1950, Viktor Glukovsky, ti Kiev, USSR, ṣe agbekale awọn ohun elo kọnkéré ti a ti mọ labẹ awọn orukọ “kankéré lati ara yanrin ilẹ” ati “sìmẹ́ǹtì lati ara ile”, ṣugbọn lati igba ti Joseph Davidovits ti ṣe ifihan ọna iṣẹda Jiopoda, isoruko ati itumọ 'Ji-Ja' ti di ohun to pọ to si n fa.. | wikipedia | yo |
Àwọn àpẹẹrẹ tí ó wà ní ìsàlẹ̀ ni a mú láti àwọn ìwé imọ-jinlẹ 2011, tí àwọn onímọ̀-jinlẹ̀ nínú oríṣiríṣi ẹ̀kọ́ kọ́.Oríṣiríṣi ìtumọ̀ ló wà fún jíọpọríboríṣiríṣi ìtumọ̀ ohun a mọ̀ sí jíọpọdafún àwọn oní ìmọ̀ Kemistri '.... | wikipedia | yo |
JiopoLima ni ilana Polymeric si-o-al, tí ó jọ ti Zolites.. | wikipedia | yo |
Ìyàtọ̀ akoko si Zolite ni pe Jiopogbádùn je Ahunphous Dipo Crystalline | wikipedia | yo |
Awọn ohun to dipo sinu Jiopoda (MicroStructure) lori iwọn kan Nano ti a se akiyesi nipasẹ tem ni awọn iṣupọ aluminosi-Odi kekere pẹlu awọn àlàfo kékèké laarin nẹtiwọọki ti o ni agbara pupọ.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n àwọn Títbi Ìṣùpọ̀ yí wà láàrín ìwọ̀n Nanomẹ́ta 5 àti 10.. | wikipedia | yo |
‘Fún àwọn oní ìmọ̀ Kemistri ohun elo fun Jipó ‘.... | wikipedia | yo |
Àdàpọ̀ AMAA fa síó4 àti alo4, àwọn iṣelọpọ tí ó sopọ ní igun mẹ́rin nípasẹ̀ oxygen pínpín bí Poly(sí(alà, tàbí Poly(sí(14-lọ-lọ) tàbí Poly(sí - DiṢílòxo) dá lórí lórí apá / Al2O3..3.. | wikipedia | yo |
Ìsopọ̀ àwọn onígun mẹ́rin yí wáyé nítorí òhun papọ̀ covalent.. | wikipedia | yo |
Nitori naa, a le pe eto apapọ jioponibí bii 'Avphous' tónípọn ti o jo ohun to le bii Crystal to ni Akojọ 3–d aluri-sili ninu.’fun awọn onímọ̀-jinlẹ àkàjinlẹ-idásí '.... | wikipedia | yo |
JiopoLima je awon eya ilana ti a sejade nipasẹ síṣopọ̀ ohun elo aluminosi-cha onigun mẹrin, pẹlu àwọn ayọni (ions) irin Aawọ (Alkali) o ni nkan se pẹlu Al onigun mẹrin.. | wikipedia | yo |
Ni ajọṣepọ, a ṣe adapópó lati apopo apakan meji, ti o jẹ ipilẹ Alailaini kan (nigbagbogbo ìyọkúrò Ṣíke- ati awọn ohun elo aluminosi-Ogbẹ ti o lagbara.. | wikipedia | yo |
Gasiymerization le ṣẹlẹ ni ìbáramu tabi iwọn otutu ti o ni agbara diẹ, nibiti ìkọ̀wé ti awọn ohun elo aise aluminosi-logoji aise ninu awọn soso ipilẹ jẹ yori si gbigbe ti awọn ẹya ti a ti fiwẹ́wẹ́ lati awọn aaye ti o nipọn sinu ipo jẹli ti o ndagba, atẹle nipa nucleation ati condensation ti ipele jẹli lati fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ kan ti o nipọn alágídí.. | wikipedia | yo |
Eṣinṣín ilẹ̀ tí wọ́n ń dá pè ní (musca Domeorísun) jẹ́ ohun tí ó ń fò, tí ó sì jẹ́ ọksn lára ẹbí ìṣerrhapha.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eṣinṣin yí wa láti ayé wẹrtoô, kí ó tó nà fọ́n ká sí orílẹ̀ àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára kòkòrò tí ó wọ́pọ̀ nínú ilé.Ìrísí rèéṣinṣin ilé tí ó bá ti dàgbà ma ń ní àwọn olómi eérú sí àwọ̀ dúdú, tí ó sì ní ilá olóòró ní ẹ̀yìn, ó nírun wẹ́rẹ́ wẹ́rẹ́ lára, pẹ̀lú iyè méjì.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ní ojú pupa tí yó kòǹgbà síta.Ìbálòpọ̀ iyèyín àti ìpamọ́ rèésinsin ilé tí ó jẹ́ àbọ̀ ma ń sábà ní àṣepọ̀ ní ẹ̀ẹ̀kan, tí ó sì ma ń gbe àtọ̀ àkọ̀ kiri láti loo nígbà tí àsìkò àti yẹ́yìn bá tó.. | wikipedia | yo |
Ó ma ń yé ẹyìn tí ó tó ọgọ́rùn ún nípa sìsábà lé ohun kan tí ó ti ń jẹrà bí onjẹ bíbàjẹ́ tàbí ìgbẹ́.. | wikipedia | yo |
Awon ẹyin yi ni won ma n yíra pada si ohun abẹ̀mí ti ko lese ti a mo si [[[Ìdin..Àwọn itọkasikòkòròàwọn eṣinṣin.. | wikipedia | yo |
Ile ti a tun nnda pe ni ibugbe jẹ ibi tabi ayé ti a le ma sun tabi gbe pẹlu awọn ẹbi wa.Ohun elo ikoleilẹ̀ lọpọ ma n jẹ ohun ti wọn ms na fi igi ati ìkì koblaye atijọ.. | wikipedia | yo |
Hanks Aàánù tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù kẹjọ Ọdún 1960 (27 August 1960) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa n kópa nínu sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Igbó as of 2017, Aàánù was Nauhànzed and became a Ghanaian.Igba Ewe rẹ̀Anuku lọ sí ilé-ìwé Loyola College, ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé alágbàwẹ̀ ẹ̀kúrú ní ilé-ìwé òbábá Polytechnic in 1981, and he was born 1960 In Ibadan.Àtòjọ àwọn sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa daylight (2001) Bitter Honey (2005)The Captor (2006)men on Hard Way (2007)Fools) on the run(2007) Desperate Amon(2006) Love AliVeradieàwọn Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Osita Iheme, MFR tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ Oṣù Kejì ọdún 1982 (February 20, 1982) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́ká tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí "Paww" látàrí ipa tó kó gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà-ìtàn PawPaw nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ n Aki na Ukwa pẹ̀lú Chinedu Ikedieze.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ìdàgbà movement Africa, èyí tí ó dá sílẹ̀ láti ṣe ríya fún àwọn màjèsín àti ọ̀dọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Áfíríkà lápapọ̀.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1988, Iheme gba àmì ẹ̀yẹ Lifetime Achievement Award, èyí tí African Movie Academy Awards fún un.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kà á sí ọ̀kan nínú àwọn òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó gbajúmọ̀ jùlọ.. | wikipedia | yo |
Chinedu Ikedieze, MFR tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá ọdún 1977 (12 December 1977 ní ìlú Bẹ́n, ní Ìpínlẹ̀ Áááá, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ nípa ipa tí ó maá n kò pẹ̀lú Osita Iheme nínu àwọn sinimá àgbéléwò pàápàá jùlọ sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Aki na Ukwa.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2007, Ikedieze gba àmì ẹ̀yẹ ìdatẹnumọ́ Lifetime Achievement Award ní African Movie Academy Awards.Àtòjọ àwọn sinimá-àgbéléwò rẹàwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Clem Ohameze jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti ń ṣeré fún nǹkan bí ogún ọdún sẹ́yìn.. | wikipedia | yo |
Clem Ohameze bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 1995.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ ní kété tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọlé rẹ̀ End Time.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tó ti tó ẹẹdẹgbẹta (500) fún ọdún ogún tí ó ti ń ṣò láti ọdún 1995 títí di àkókò yìí.Igba Ewewon bí Clem Ohameze lọ́hìn jádarà Oṣù kẹfà ọdún 1965 (27 June 1965) nílùú Port Harcourt, ní ìpínlẹ̀ Rivers, lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Holy Family Family/Baptist High School fún ẹ̀kọ́ ilé-ìwé girama.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Institute of Management Technology, Enugu, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbi tí ó ti kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú dilòpọlọ nínú ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀.. | wikipedia | yo |
Bakan naa o lo si University of Port Harcourt nibi ti o ti kawe dinko eri ninu dìgírì ninu imọ ayika ati eniyan (iṣẹàwùjọ ati ANThpọ|X) lodun 1989.. | wikipedia | yo |
Bakan naa, o tun kawe gboye digírì keji ninu imo iṣẹgun abo ati ayika ni oke-okun ni BuUC, ni London lodun 2010.Àwọn Ìtọ́kasí.àwọn oṣere ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Moba Stars football Academy ile-eko ijinle ere idaraya ti o da ni Ipinle Akwa Ibom, Nigeria.. | wikipedia | yo |
Ile-eko giga naa da ni 2002 o si fi aṣẹ nipasẹ Gomina ti tele ti Ipinle Akwa Ibom, Akpan Isemin.. | wikipedia | yo |
Ile-ijinle yii da pelu ero-ise iṣere ati idagbasoke awon elere idaraya ni Nigeria.. | wikipedia | yo |
Ile-ijinle wa ni a mo fun dida opolopo awon osere U-17 fun egbe afẹsẹgba orile-ede Naijiria labẹ-17.. | wikipedia | yo |
ti yan ile-iwe giga fun ile-eko giga Grassroot ti o dara julọ ni ile-iṣere ere idaraya ti Ilu Naijiria 2019.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Láfiají Okuneye bílẹ̀kis jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìlera, ọmọ bibi Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
A bí Bonkis ní Ọjọ́ Kejì Oṣù Kejì Ọdún 1972 ní Erékùṣù ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ Gíwá ilé ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni àgbà ti Adéníran Ògúnsànyà College of Education.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |