cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránṣo ti ìgbàlàde yí pẹ̀lú ìwúrí ara ọ̀tún láti ọ̀dọ̀ ìyá tó bí wọ́n lọ́mọ tí òun náà jẹ́ aránsọ jẹun.. | wikipedia | yo |
Pupọ ninu aṣọ tí àwọn ibeji yi n ran ni o ma ń ṣe itan kan tabi omiran.Àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bi sí ìlú Ìbàdàn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
Ó ti tó ọgbọ̀n (30) tí ó tí ń ṣiṣẹ́ sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Oun ni Gomina egbe Tiata ti won n pe ni Theater arts and motion Pictures Practitioners Association of Nigeria (Tampan) ti ẹka ipinle Oyo.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Wàáris tí ìtumọ̀ rẹ̀ lédè Yorùbá jẹ́ àrólé ni eré sinimá onípele aládùn lédè Hindu láti orílẹ̀ èdè Indian tí wọ́n gbé jáde lọ́dún 2016, tí wọ́n máa ń ṣe àfihàn rẹ̀ lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn.. | wikipedia | yo |
Àwọn olórin Nooran Sisters ti kọrin nípa àkọlé eré yìí.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ àwọn Anacha Aodesh, Olú-ẹ̀dá ìtàn eré yìí, arti Singh àti Sof tou tí ó tún kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dá ìtàn nínu eré yìí.. | wikipedia | yo |
Àwọn tí wọ́n tún kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn nínú Wàáris ni; Anand Diws Aky, Aky Dogra, Swati bàaÀwọn Ẹ̀dá-Ìtàn Olú-ẹ̀dá ìtàn arti Singh kópa bí Amba pawá pawá Shetty kópa Bí Manp Singh pawá pawá (FM 2017) Mọ́mìwáni kópa bí I Raj 1982 Ẹ̀dà-ìtàn pàtàkì an Ance 2019 as Harjeet Singh kápá Yàrás Kale kópa Bí Mo 1982 Doy Do kópa bí gan ] Mo Alvez Sanvez kópa Bí In Ana (in Val Chhe Chmo Suf Mo W (FM Worif (UK) kópa bi Mo 1982 Wa Baroko kópa bi Gunpa Mo fi Mo kópa Bí Irú Africa PA San Sanan kópa Bí Mo pawá FM La Red Bi Amwa kópa _*Wa Bá Balv Sansha Man Sanagor kópa Bí Ni Chru Wata Wa kópa B FM Iq K 21 A 2017ran FM Giebi, To Aoni kopa bi E Manp Lop Lo Numan (W Wa kópa tálákà Rajwa N India Wa India Khan Ọmọdéhan A 1982 Irú 2 K N W Ítálì Young Gun Ana O Odunka Mo Ki kopa The Red K Koni Don kópa B 1982 K K K kópa La La Olu W W N & M kópa Mo Mo Mo 2016 FM Yàrá arúgbó Bí Ọ̀rẹ́ Rajya Wa Wa A kópa Bi Yàrá Kaila B Koba Koko Wa D | wikipedia | yo |
furà jẹ́ ońjẹ tí a fi ọkà bàbà àti àwọn èròjà míràn ṣe tí ó wọpọ láàrín àwọn ẹ̀yà Fulani àti Hausa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Niger.Àwọn Fulani ní wón ní ẹ̀yà òtẹ́ ìbílẹ̀ yí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì ma ń ṣe fura dà nùnù pẹ̀lú lílo àgbàdo tàbí ọkà bàbà tí wọ́n yóò sì fi wá rà ti wò fún láti ara màlúù poo pọ̀ fún mi mu.Àwọn ìtọ́kasíàwọn onjẹ.. | wikipedia | yo |
Lẹ́tà gbẹ̀fẹ́ ni irúfẹ́ lẹ́tà tí a má ń kà sí àwọn ará, ẹbí, ọ̀rẹ́ àti iyèkan ẹni.. | wikipedia | yo |
Àdírẹ́sì kan ṣoṣo ni ó má ń wà nínú lẹ́tà gbẹ̀fẹ́, tí àdírẹ́sì náà yóò sì jẹ́ ti olùkọ́ lẹ ni a pa ọ̀tún ojú-ewé ìwé wa.. | wikipedia | yo |
Tọ́n lẹ́tà lè ka àdírẹ́sì rẹ̀ ní ìlànà méjì; àkọ́kọ́ ní ìlànà ìòró àti ìlànà Oníbú.. | wikipedia | yo |
Èyí lè gba ọ̀nà oríṣiríṣi wa bí onọ́n lẹ́tà bá ṣe fẹ́.. | wikipedia | yo |
Yálà ó fẹ́ pilẹ̀ lẹ́tà kíkọ ni tàbí ó fẹ́ fèsì sí lẹ́tà tí àwọn ènìyàn rẹ̀ kọ sí bóyá látòkèrè ni tàbí nítòsí.. | wikipedia | yo |
Láti ìfáàrà sí ibi tí ó pín sí ní àárín lẹ́tàlẹ́yìn èyí ni olùkọ́ lẹ́tà yóò ṣe ìkadi lẹ́tà rẹ̀ pẹ̀lú “Èmi ni ọmọ yín tòótọ́ tàbí tèmi ni ti yín ní tótọ̀ọ́, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.A.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Lẹ́tà Agbẹ́fẹ́ ní oríṣi lẹ́tà kejì tí a ma ń kọ sí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ àdáni tàbí ti ìjọba, yálà nígbà tí a bá ń wáṣẹ́ tàbí fẹ́ gba ohun kan tàbí òmíràn ní ọwọ́ irúfẹ́ ènìyàn bẹ́ẹ̀.. | wikipedia | yo |
O fi han wipe irufe eniyan yi ko ni ra ye lati ma ka itan tabi ka yeye tabi awada eyikeyi, nitori iṣẹ wọn pọ ju awọn nka wọnyi lọ.. | wikipedia | yo |
Awon eniyan yi le je oga agba, olootu agba, oga olopa, gomina, Aare orile-ede ati bee bee lo.Awon ohun ti o wa ninu lẹta aife niadi meji eyiokan la pa otun, okan losi.. | wikipedia | yo |
Èyí tí yóò wà ní apá ọ̀tún yóò jẹ́ ti olùkọ́ lẹ́tà, ti èyí tí yóò wà ní apá òsì yóò jẹ́ àdírẹ́sì ẹni tí ó fẹ́ gba lẹ́tà kà.. | wikipedia | yo |
Gbogbo ìparí ọ̀rọ̀ nínú àdírẹ́sì ni ó gbọdọ̀ àwọn àmì ìdànù dúró díẹ̀ àti ìdáná-dúró pátá pátá.. | wikipedia | yo |
Ìfáàrà tí o n tọ́ka ohun tí a fẹ́ kí wọ́n ṣe fún wa gbọ́dọ̀ dá dúró.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Silabọ́ọ̀sì (; jẹ́ ìlapa-èrò ìṣe ) tàbí àkóónú kọ́kọ́ ìṣe inú ètò ẹ̀kọ́ kan tí a fẹ́ fi kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́.. | wikipedia | yo |
Ìko ati je ki oluko o ni ìkápa lori ohun ti o fe ko, ki awon akekoo naa o sin le gbáradì fun koko eko to kan ki won le se às̩eyege keyin eko naa.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Nínú ètò ẹ̀kọ́, kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ni ó túmọ̀ sí pàápín kókó ètò-ẹ̀kọ́ nínú ìlànà ìkọ́ni.. | wikipedia | yo |
ó tún lè jẹ́ àgbékalẹ̀ pàtó tí ó dá lé ìrírí àti òye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ìkọ́ni tààrà... | wikipedia | yo |
Kété ma ń kọ kókó iṣẹ́, ohun èlò ikẹkọ ati ọna iṣe ìgbéléwọ̀n fun eto ìkẹ́kọ̀ọ́ naa.Ọ̀nà ti kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù pin si kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù alákọsílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Èyí ni kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù tí a kọ sílẹ̀, ṣe àgbéyẹ̀wò rẹ̀, tí a sì pọn ní dandan láti máa tẹ̀lé nínú ìlànà ètò ẹ̀kọ́ wa gbogbo, yálà ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama, tàbí Fásitì.. | wikipedia | yo |
Èyí ni kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù tí a kò ké gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ti dún, àmọ́ òun ni ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a kọ lọ́nà ọ̀rá.. | wikipedia | yo |
Àwọn ẹ̀kọ́ tí a lè kọ́ ní abala ètò ẹ̀kọ́ dífoju ní àṣà , iṣẹ́àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yálà nínú ilé-ẹ̀kọ́ ni tàbí iyàrá ìkẹ́kọ̀ọ́. | wikipedia | yo |
Eyi ni ṣe pẹlu ere idaraya, orin kikọ, ati bẹẹ bẹẹ lọ, ti awọn akekoo yoo ri eko kan tabi omiran mu nibi iṣẹ naa.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
ÀGBÉKALẸ̀ Ẹ̀KỌ́ NI O DÁ LÉ ifọsí wẹ́wẹ́st ìlapa ÈRÒ OLÙKỌ́ TI Ol AGER TI PèMO Kalẹ̀ NÍ KÍKÚN LÓRÍ LÈ BÍ Ẹ̀KỌ́ YÓÒ ṢE YẸ ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ NÍNÚ ìyàrá ikẹkọ.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ojojumọ ni Olukoo gbọdọ ma kọ ìlapa ero ẹkọ fun asiko ikẹkọ kọọkan ṣaaju ki o tọ wọ iyara Ìkẹ́kọ̀ọ́.. | wikipedia | yo |
isedale rẹwọn gba orin-iyin orile ede Naijiria ti akole re n je "Àríṣe o Com."[ots" ti itumo lede Yoruba je "Ẹ dide ẹyin ara" wole gege bi orin-iyin orile ede naa lodun 1978, ti won sin fi i ropo orin iyìn atijọ ti akole re n je "Nigeria, we hail Ańgẹ́lì", ti itumo re lede Yoruba je "Naijiria, Ayin O" it was adopted in 1978 and replaced the previous National anthem, "Nigeria, we hail ajele1" | wikipedia | yo |
ohun orin-ìyìn jẹ́ àpapọ̀ ọ̀rọ̀ àti awẹ́-gbólóhùn tí wọ́n pò pọ̀ láti márùn-ún àwọn orin ìyìn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n fi díje àpapọ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ akọrin àwọn ọlọ́pàá lábẹ́ ìṣàkóso Benedict E.. | wikipedia | yo |
Odiase ni won pàwọn pọ̀ ti won so o di orin-ìyìn orile ede Naijiria ti a n ko bayii.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé abala méjì ni orin-ìyìn yìí wà, abala àkọ́kọ́ ni wọ́n ṣáábà máa ń kọ, ṣùgbọ́n nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, wọ́n máa ń kọ́ abala kejì gẹ́gẹ́ bí "Orin ìwúre fún Nàìjíríà” ní àwọn ayẹyẹ mìíràn.Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lédè Yorùbá, abala àkọ́kọ́ díde ẹ̀yín ara wa jẹ́ ìpè Nàìjíríà ka fífẹ̀ sin ilé wa l'òkun àti ìgbàgbọ́ kí ìṣe àwọn akọni wa, kó má ṣe já sásán ká sìn in tọkàn tara ilẹ̀ Totàbi, àtàlàáfíà sọ dọ̀kan-ìyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lédè Yorùbá abala Ikeji Ọlọ́run Ẹlẹ́dàá tọ ọ̀nà wá han aṣáájú kó ó wá Motítòkó iba yíyí sí ìkà wọ́n jẹ́ pípè pípè wọ́n dẹni gíga kalàáfíà òun ètò lè jọba nílé wa.’A orin-ìyìn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lédè Gẹ̀ẹ́sì àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ti wọn tun maa n pe ni ajọdun Gkare Eko ti gbogbo eniyan mọ si Lagos Carnival lede Gẹẹsi, jẹ ajọdun ti o gbajumọ julọ iwọ oorun Afirika.. | wikipedia | yo |
Àjọ̀dún yìí máa ń wáyé nígbà àjọ̀dún Lagos Lagos Black Heritage Festival, èyí ni àjọ̀dún alárinrin Agbasa àti iṣẹ́ ìbílẹ̀ ga tí ó máa ń wáyé lọ́dọọdún.. | wikipedia | yo |
Isedalẹ ajọdun fanti bẹrẹ ni Erekusu Eko nigba isejoba awon oyinbo amunisin ati asiko okoowo eru ni Saẹ́ńtúrì ṣiṣan seyin, nigba ti awon eru ti won ko lo si orile ede Brazil pada bo si ile.. | wikipedia | yo |
Ọdún 2010 ni wọ́n tún bẹ̀rẹ̀ sí ní dùn yìí padà lẹ́yìn tí wọ́n kò ṣe é fún ẹgbẹlẹmùkù ọdún.. | wikipedia | yo |
Erékùṣù Èkó ní ìpínlẹ̀ Èkó ni àjọ̀dún yìí ti máa n wáyé.. | wikipedia | yo |
Orísirísi ìmúra àṣà pẹ̀lú aṣọ alárànbara ni àwọn ènìyàn máa ń wọ̀ lásìkò àjọ̀dún yìí.. | wikipedia | yo |
Orísirísi ijó, ìlù àti orin ìbílẹ̀ ni ó máa ń wáyé lásìkò ọdún yìí.. | wikipedia | yo |
Amulú asa Yoruba ati Brazil ni won maa n gbe laarin nigba odun fanti ni Erékùṣù Eko.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Allwell Ademola tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọjọ́ kẹsàn-án Oṣù Kẹjọ Ọdún 1983 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí, ònkọ̀tàn, akọrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ-ọmọbìnrin adájọ́-àgbà jùlọ àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, Adájọ́-Àgbà, olóògbé AdéTokunbo Ademola .Ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbà èwe rẹ̀ó kàwé gbàwé ẹ̀rí ní Ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tó gúnwà sí Ilé-Ifẹ̀, OAU.. | wikipedia | yo |
Allwell bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò láti ewé ṣùgbọ́n ní ọdún 2008 ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò, lára àwọn sinimá-àgbéléwò tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ síta ní; jádò Ọjọ́, etí kẹta, ọmọ èmi, You.. | wikipedia | yo |
Or I, Aye Keji.Àtòjọ Diẹ ninu àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀[[ayé keji] Idajo tiwa's Bìrẹ́pọ̀ge (Àmódi) Odere Olonjẹ Omo Ẹmi Side Chic Squ false Flag Ki'won Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìkẹ́kọ̀ọ́ òkèrè ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí wa fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ọ̀nà wọn jìn, tí wọ́n sì kọ́ sí ní ànfàní láti dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn nílé ẹ̀kọ́.Ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí má ń dá lé fífi àwọn àkóónú, kókó, àti àwọn àtúpalẹ̀ ẹ̀kọ́ gan an ránṣẹ́ sí akẹ́kọ̀ọ́ ní ibi kíbi tí ó bá wà lórílẹ̀ àgbáyé, nípa lílo àpò ìfìwé -ránṣẹ́. Àmọ́, láyé òde òní, ìlànà ìkìní yí ti gbóná àrà ọ̀tọ̀ nípa kíkékókóoórì ẹ̀rọ ayélujára.. | wikipedia | yo |
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Okere lè jẹ́ alasinpo tí akẹ́kọ̀ọ́ yoo ma kẹ́kọ̀ọ́ láti ọ̀nà ìnà tí yoo sì tún ní ànfàní láti dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ nínú ìtara ìkòrí.àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Mallam Aliyu Mai-Bornu tí wọ́n bí ní ọdún 1919, tí ó sì ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 (1919 – 23 February 1970) jẹ́ okùna-gbòngbò onímọ̀ nípa ètò ọrọ̀ ajé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni ọmọ orile ede Naijiria akoko to je gomina ile ifowopamo-agba ti Naijiria.Awon itọkasiawon araNaijiria.. | wikipedia | yo |
Clement ńyọng Isong, CFR ti wọn bi ni ogunjo osu kerin odun 1920, O sin ku ni ọjọ kokandinlogbon osu karun-un odun 2000 (20 April 1920 - 29 May 2000).. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti onímọ̀ ilé-ìfowópamọ́ tí ó jẹ́ Gómìnà ilé ìfowópamọ́-àgbà ti Nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1975 nígbà ìṣèjọba ológun Ọ̀gágun Yakubu Gowon.. | wikipedia | yo |
Wọ́n wá padà dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River lọ́dún 1979 sí 1983.Ìgbé ayé rẹ̀ a bí Isong ní ọjọ́ ogún oṣù kẹrin ọdún 1920 ní Èkét, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Fásitì Kọ́lẹ́ẹ̀jì Ìbàdàn, lowa Werestẹ̀lẹ́ College, Mount Pleasant, Iowa, àti Olùìjà Graduate School of Arts and Sciences, níbi tí ó ti gba Ph.D.. | wikipedia | yo |
O jẹ olukọni nipa ọrọ -ajé ni University of Ibadan ṣaaju ki o to darapọ mọ Central Bank of Nigeria (CBN) gẹgẹbi akọwe, titi ti o fi di oludari iwadii.. | wikipedia | yo |
Ótún wà pẹ̀lú International Monetary Fund gẹ́gẹ́bi onimọran ni ẹ̀ka Karinrinṣíkọ̀ rẹ gẹ́gẹ́ bi gómìnà banki CBN Yakubu Gowon yan Isong Gomina CBN ni oṣu kẹjọ ọdun 1967, ọfiisi ti o wa titi di oṣu Kẹsán ọdun 1975.. | wikipedia | yo |
Ohun kan na lo je gomina banki Naijiria ni asiko ogun abele ti Biafra (1967-1970) ati nigba ti epo rọ̀bì búrẹ́kẹ́ ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ni akoko re Naijiria ya fun jije gbese.O tako bi orile-ede Naijiria se n se iko ìṣura jo si oke okun lai lai fi se idoko si bi to ye, bi o tile je wipe ijoba wole wa ni eto amayederun ni orile-ede Naijiria-ede gominaàwọn gomina ipinle Cross River.. | wikipedia | yo |
Ọ̀jọ̀gbọ́n babaGánà Umara Zulum tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1969 (August 26th, 1969) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti olóṣèlú ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Borno lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dìbò yàn án lọ́dún 2019 lábẹ́ ásìya ẹgbẹ́ òṣèlú APC.Igba Ewe kòmo bi a ti sọ ṣaaju, wọn bi babaGánà lọjọ́ kerindinlogbon Oṣu Kẹjọ Odun 1979 ni ijoba ibile Mafa ni Ipinle Borno .Àwọn Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1969àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno.. | wikipedia | yo |
Jẹ́ ìṣèjọba tí ó kéré jùlọ, tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìpín agbègbè kọ̀ọ̀kan láti jẹ́ kí ètò ìṣèjọba pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́e sún mọ́ àwọn ará ìlú.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ ìpín ìṣèjọba tó kéré sí ìjọba ìpínlẹ̀ àti ìjọba àpapọ̀, pàápàá pàápàá jùlọ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
lábẹ́ ètò ìṣèjoba àpapọ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ìjọba ìbílẹ̀ maa n wà lábẹ́ àkóso yálà ìjọba ìpínlẹ̀ tàbí ìjọba àpapọ̀.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìgbìmọ̀ Oiretà ni Ìgbìmọ̀ tí ó túmọ̀ sí “Ìgbìmọ̀ tí ó ń rí sí ìwádí ìlòdì sí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.. | wikipedia | yo |
jẹ́ ìgbìmọ̀ tí ọ̀gágun àti ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Olusegun Obasanjo fu lọlọ lẹ́yìn ìwòmi ìjọba ìjọba ológun tí ó ti jẹ́ gàba ní orí orílẹ̀-èdè Nàíjíríà títí di ọdún 1998.. | wikipedia | yo |
In terms of Reconmoni, the Commission also worked towards unidou communities previously in conflict.. | wikipedia | yo |
Ojú ṣe ìgbìmọ̀ yí ni láti ṣe ìwádi ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ti àwọn ìjọba ológun ti tẹ̀ lójú lásìkò tí wọ́n ń jẹ gàba, kí wọ́n sì pẹ̀tù sí aáwọ̀ náà, pàá pàá jùlọ kí wọ́n mú ìrẹ́pọ̀ wá láàrin ìlú, agbègbè àti àwùjọ ti yáne yanrìn ti wà tẹ́lẹ̀.Ìpilẹ̀ wíwà ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà lábẹ́ ìjọba amúnisìn títí di ọdún 1960 tí a gba òmìnira lọ́wọ́ ìjọba Hgẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ìgbòmìnira yí, oríṣiríṣi dàgbà-Sód Ogun Abẹ́lé ni ó bẹ́ sílẹ̀ tí ó sì mú ìfàsẹ́yìn bá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti wà ní ìrẹ́pọ̀ àti ìṣọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Àwọn ìṣòro bí ìjà ẹ̀sìn, ẹlẹ́yà-mẹ̀yà, tí ó mú kí ogun abẹ́lé tí ó bẹ́ sílẹ̀ pẹ́ nílẹ̀ títí di ọdún 1970, ni èyí tí ó mú kí orílẹ̀-èdè náà ó wà ní abẹ́ ìṣàkóso ìjọba ológun, tí ogunlọ́gọ̀ ẹ̀mí sì ṣófo.. | wikipedia | yo |
bí orílẹ̀-èdè yí ṣe wá lábọ̀e ìṣàkóso ìjọba ológun apàṣẹ wàá, oríṣiríṣi ìdìtẹ̀ gbàjọba ni ó ṣẹlẹ̀, ni èyí tí ìdìtẹ̀-gbàjọba ọdún 1966 bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, títí di àsìkò ìjẹ gàba Ọ̀gágun Ibrahim Babangida ti rògbòdìyàn ìdábọnu tí gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà di yàn ní ọdún olóyè MKO Abiola.. | wikipedia | yo |
Ìṣẹ̀lẹ̀ yí ni ó sì Le Babangida kúrò lórí ìtẹ́ ní ọdún 1993.. | wikipedia | yo |
Wàhálà òun Rògbòdìyàn tún tẹ̀ síwájú nígbà tí Ọ̀gágun Sani Abacha gba ìjọba lẹ́yìn Babangida tí òun náà sì papò dà ní ọdún 1998.. | wikipedia | yo |
IKÚ Abacha ni ó sì gbé ọ̀gágun Olusegun Obasanjo dé ipò gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ nínú ìjọba àwa arawa.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kẹ̀kẹ́ alùpùpù) ní kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ méjì tí ó ń lo engini àti epo bẹntiróò láti fi rìn ní ojú pópó.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fún kẹ̀kẹ́ alùpùpù yí ní orúkọ ìbílẹ̀ rẹ̀ ọ̀kadà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní àfijọ ọkọ̀ òfúrufú kan ọ̀kadà Air tí ó wà ní àrọko ìpínlẹ̀ Benin àmọ́ tí kò sí mọ́.. | wikipedia | yo |
bẹntiróò (/pjẹuntstaəəb)} jẹ́ ọ̀kan lára ohun àlùmọ́nì kan tí ó ní àwọ̀ méjì awo dúdú àti omi ara yẹ́lò tí wọ́n ma ń wà jáde lábẹ́ ilẹ̀.. | wikipedia | yo |
Wọn ma ń fẹ ohun àlùmọ́nì yí sí orísirísi ọ̀nà, ni èyí tí a ti ri epo bẹntiróò àti àwọn mìíràn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n má ń dáFIFI oríṣiríṣi epo lọ́pọ̀ láti ara ìdará nípa lílò ohun tí E- ń pè ní (Frayẹ̀wò Distives ní sí 80 di ni pé * * * * * ohun ní wọ́n lọ́wọ́ ní ọdún rẹ̀ * • pẹ̀lú ọdún rẹ̀ ní wọ́n lọ́wọ́ ní ọdún ( Wami tí ó pè ní ọdún ( ṣorí ní wọ́n ní wọ́n lọ́wọ́ ní ọdún rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ sí ọdún yìí ní ó lọ́wọ́ ní wọ́n pe ní ọdún York ní ọdún yìí sí pẹ̀lú ní wọ́n maa sí ọdún rẹ̀ tí ó tún sí ọdún rẹ̀ ní ọdún tí wọ́n maa sí ìdá orí orin rẹ̀ sí ìbúro ní lílò ohun rẹ̀ ní wọ́n maa ń gbádùn ọdún rẹ̀ ní ọdún rẹ̀ tí ó maa ní FI ní wọ́n maa di pé ní wọ́n maa sí ọdún rẹ̀ sí ara omi ní lílò ohun ní ọdún tí ó maa sí ( díohun ní ti ọdún rẹ̀ pé ni ọdún ( ọdún * ní wọ́n ọdún rẹ̀ * * ní ọdún * | wikipedia | yo |
Lára bẹntiróò ni wọ́n ti ma ń yọ epo káróṣì, aṣphalt àti kẹ́míkà tí wọ́n n pè ní reagent tí wọ́n n lò láti fi pèsè àwọn ike, àti ogún kòkòrò oriṣiriṣi.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Èyí ni àtòjọ àwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè Cameron láti ìgbà tí wọ́n ti gba òmìnira lọ́wọ́ orílẹ̀-èdè Faransé lọ́dún 1960 títí di òní yìí.. | wikipedia | yo |
Ènìyàn méjì péré ló ti jẹ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè Cameron lẹ́yin òmìnira wọn.. | wikipedia | yo |
O ti wa lori oye lati ojo kefa osu Kọkànlá odun 1982atojo awon Aare orile-ede camelọwọ́roko ìdámọ̀ awon egbe oseluawon Aare orile-ede Cameronawon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn Azerbaijan jẹ́ àwọn ìwé ìròyìn ọlọ́jọ́ojúmọ́ tí ó ń jáde ní àti orílẹ̀-èdè Azerbaijan.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀yin jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí ó le koko tí kìí ro tí ó má ń hù jáde láti inú èrìgì ninu ẹnu tí a má ń lọ láti jẹun tabi fọ́ egungun.. | wikipedia | yo |
Gbogbo ẹranko tí ó ní egungun lẹ́yìn tí wọ́n sì ma ń rún ońjẹ lẹ́nu ni wọ́n ma ní eyín.. | wikipedia | yo |
nígbà tí púpọ̀ nínú wọn ma ń fi ẹ̀yìn sóde tàbí dáàbò bo ara wọn lọ́wọ́ ewu.. | wikipedia | yo |
Àwọn onímọ̀ fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ẹ̀yin kìí ṣẹ́ egungun rárá bí ó ti wulẹ̀ kì ó mọ́, àmọ́ ẹ̀yin jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn tíṣù kán tí wọ́n ń pè ní ekùúderm ni wọ́n para pọ̀ di ẹ̀yìn.. | wikipedia | yo |
Ìrísí ẹyin ní ara gbogbo ẹranko elégungun ma n jọra wọn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìyàtọ̀ ma n wà níbi títọ jo wọn.Ẹyin gbogbo àwọn ẹranko elégungun sábà ma n fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin, bákan náà ni ó ma ń rí lára àwọn ẹja àti àwọn Ọọ̀ni.. | wikipedia | yo |
Àmọ́, lára àwọn ẹja kan tí wọ́n ń pè ní tẹ́lẹ̀Óst ìta egungun ẹnu wọn ni eyín wọn ma ń hù sí, lára àwọn aláǹgbá inú apá kan orí egungun ẹnu wọn ni eyín wọn má wà.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn ẹja oní kẹrẹkẹrẹ bí ẹja owù, ẹ̀yin wọn sopọ mọ Ligaments tí ó nipọn tó sì sopọ mọ kẹrẹkẹrẹ àrùngbọ̀n wọn.híhù ẹ̀yìn láàrín àwọn ẹrankoọ̀ ẹ̀yin láàrín àwọn ẹranko elégùn ma ń jẹ bá ka ka n náà, àmọ́ ìyàtọ̀ ma ń wa láàrín ipò àti bí wọ́n ṣe ń hù láàrín ẹranko sí ẹranko.. | wikipedia | yo |
Kìí ṣe àwọn ẹranko nìkan ni ó ma ń hu ẹyin, àwọn ẹja àti ẹran inú omi náà ma ń hu ẹ̀yìn.. | wikipedia | yo |
.Ẹyin kìí sábà hù nínú ẹnu nìkan gẹgẹ bí àwọn ẹ̀yà ẹranko kan ṣe ma hù ti wọn.. | wikipedia | yo |
Híhu ẹ̀yin láàrín àwọn ẹja sábà ma ń wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ẹnu wọn, nígbà tí ti àwọn kan so mọ́ ẹ̀gbẹ́ èrìgì wọn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Luwòó gbágídá jẹ́ Ọba obìnrin àti Ooni àkọ́kọ́ fún ìlú ilé-Ifẹ̀ tí ó jẹ́ orírun gbogbo ọmọ kóòtù-oòjíire.Ìtàn Sepwòó jẹ́ ẹni àAbiyì, arẹwà, onímọ̀-tótó àti Akinkanku obìnrin.. | wikipedia | yo |