cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ọjà ìlú Ọjà Okòó Ìlú tàbí Ọjà ọ̀bánì ibi tí kárà-kátà lórí oríṣiríṣi lórí ohun kóhun tí ènìyàn bá fẹ́ rà ti ń wáyé nípa lílé ọjà sílẹ̀ẹ fún títà.. | wikipedia | yo |
Látorí gbogbo ohun tí ẹnu ń jẹ́ bí ata ẹ̀fọ́ Gari àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ohun tí ara ń wọ̀ bí bàtà, fìlà, aṣọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Irúfẹ́ ọjà yí ma ń sábà wà ní iwájú àfin ọba.Ọjà okoèyí ni ọjà tí ó dá lórí ohun irè oko lásán.. | wikipedia | yo |
Irè oko yi lè je ẹ̀fọ́, ata, iṣu àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọjà wọ̀nyí ni wọ́n ma ń kó wá láti tà ní inú Ọjà Àárín Ìlú.Ọjà ìgbà-lódéèyí jẹ́ ọjà tí wọ́n ma ń rà la orí ẹ̀rọ ayé-Mé-jára láti inú ilé ẹni.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún ma ń ko àwọn àgbàọ̀ kan lọ́nà àrà ọ̀tọ̀ tí wọn yóò sì pàtẹ ọjà tí wọ́n fẹ́ tà síbẹ̀, àwọn ọjà wọ̀nyí ma ń yàtọ̀ sí irúfẹ́ ọjà tí a lè bá pàdé ní Ọjà Ìlú tàbí Ọjà Ọba, nítorí àwọn Ọjà tí ôò bá pàdé níbẹ́ẹ̀ kìí ṣe Ọjà Adékò Wa, bí kìí ṣe àwọn Ọjà inú Ọ̀rá (NYlon) tàbí Ọjà inú ìké tí wọn kìí le sílẹ̀ lasan.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọjọ́ ọ̀sẹ̀ Yorùbá jẹ́ ònkà tí a fi ń ṣe ìṣírò iye ọjọ́, ọ̀sẹ̀, oṣù àti ọdún ní ilẹ̀ Yorùbá gẹ́gẹ́ bí àwọn elédè tó kù lágbàáyé ti ní tiwọn náà.. | wikipedia | yo |
jẹ́ ojo tí ó bẹ̀rẹ̀ ọjọ́ òsẹ̀ Yoruba, nítorí wípé ó jẹ́ ojo kini nínú òsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní ìbámu pẹ̀lú òǹkà ọjọ́ ọsẹ̀ láomì bí tí ó wà nínú ìtàn Àtẹnudẹ́nu Yorùbá wípé ìrànwọ́ Yorùbá ṣe wá láti ilé larubawa. ajé ajè ní ó jọ ti a ma ń dá iṣẹ́ aje tí a sì ma ń mú iṣẹ́ òwò pẹ̀lú ní ilẹ̀ Yoruba, oun sí ni ilé kejì nínú òsẹ̀. Ọ̀gun ní ọgun kẹta nínú ọ̀sẹ̀ ẹ̀sẹ̀ Yoruba. Ọjọru onírù náà ni ojo tí àwọn ènìyàn ma ń sábà ma ni ojo ń sạba ọmọ ti o ṣe gbogbo ohun gbogbo ohun gbogbo ohun ẹ̀sẹ̀ ọ̀sẹ̀ ọ̀sẹ̀ ọ̀ṣẹ ní ojo kẹfà tí gbogbo ènìyàn ma ń pe ni pé omi. pé ti ó yẹ ní ó lá ní ó ṣàmọ̀ ọ̀mọ̀ ọ̀sẹ̀ ọ̀sẹ̀ ọ̀mọ̀.. | wikipedia | yo |
Ọ̀sẹ̀ohun èlò tí à ń lò láti fi fọ ohun tí ó bá ṣeé ṣe ìmọ̀ tótó, gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀ tótó ara, aṣọ, ilẹ̀, abo àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun èlò yí lè jẹ́ ohun tí à ń lò nínú ilé tàbí ní ìta, ilé tàbí ilé iṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Bí a bá lo ọṣẹ fún ìmọ̀ tótó, ó ma ń yọ ìdọ̀tí òun ẹ̀gbin kúrò ninu ohun tí a bá fi ọṣẹ fọ̀ tabi kí ó mú àdínkù bá irúfẹ́ ìdọ̀tí bẹ́ẹ̀.. | wikipedia | yo |
A ma ń lo ọṣẹ fún ìmọ̀ tótó pẹ̀lú ìranowó omi, nítorí ọṣẹ nìkan kò ṣéé dá lọ láti fi fẹ́ nkan.Oríṣi ọ̀sẹ̀ tó wàláyé àtijọ́, ọṣẹ ìgbámú ni gbogbo ènìyàn mọ̀ tí wọ́n sì ń lò.. | wikipedia | yo |
Ànì Láyé òde oní, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ti jẹ́ kí a má lo ọ̀sẹ̀ olómi, àti ọ̀sẹ̀ oníyẹ̀fun., ọmọ ènìyàn ti ń lo ọ̀sẹ̀ láti ayébáyé fún iṣẹ́ ìmọ́ ìtọ̀ àyíká òun ara wọn.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àjàkálẹ̀ àrùn nipha jẹ́ àrùn kan tó jákè jáko ní kókó fojufoju nípha ń ṣókù rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àrùn yí má ń fojú hàn lára ẹni tí ó bá kó nípa kí ẹni náà ó ní àìsàn ibà,ìkọ́, orí fífọ́, àìlè mí kanlẹ̀ ati iyè meji èyí tún lè mú kí àlásìn yí ó dákú lọ gbọnrangandan.Ohun tí ó ń ṣokùnfà àrùn yíkòkòrò àrùn nipha ní ó jẹ́ ọ̀kan nínú ẹbí kòkòrò tí ẹniparóòsìróòsì ti ma ń gbé nínú ẹ̀jẹ̀ ohun abẹ̀mí.. | wikipedia | yo |
Kòkòrò àrùn fojufoju yi ni ó á lè ko nípa jíjẹ lálara èso tí ẹyẹ àdán bá ti fẹnu bà.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, àrùn yí le tàn kálẹ̀ láti ọ̀dọ̀ ọmọnìyàn sí ọmọnìyàn tàbí ẹranko sí ẹranko, bákan náà láti ọ̀dọ̀ ẹranko sí ènìyà àti ènìyàn sí ẹranko nígbà tí a bá ní ìfaragbà yálà èémí, ẹ̀jẹ̀, ṣinṣin ẹni tí ó àrùn yí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .. | wikipedia | yo |
Iṣẹwá arun yi lo m n da le ori ifiifilede iwadi ti o ba jade lati iyara àyàfiki jade.sise iwosan ati ona ipese oogun re titọ alaisan ti o ni arun nipha ni oludari itoju to peye.. | wikipedia | yo |
Ni asiko odun 2018, kòì tii si oogun kan pato fun itoju arun naa.. | wikipedia | yo |
Àmọ́, ṣíṣọ́ra-ẹni nípa sísúnmọ́ ẹyẹ àdán, ẹlẹ́dẹ̀ àti kí a má jẹ dàbínù tútù ní ọ̀nà kan pàtàkì tí a fi lè ṣọ́ ara wa kúrò níbi ìkọlù àrùn náà.. | wikipedia | yo |
àwọn tí wọ́n kó àrùn nípa ní ọdún 2018 ń lọ sí nkan bí ọgọ́ta ó lé mẹ́wàá ti ìdá 75 nínú àwọn wọ̀nyí sí dèrò ọ̀run.. | wikipedia | yo |
Ní inú oṣù karùn ún òdù 2018, yí kan náà, àwọn .ẹ̀tàdínlógún ni wọ́n gbékúrú jẹ lọ́wọ́ ẹbọra ní ìpínlẹ̀ ké rà lá ní orílẹ̀-èdè India.Ìtàn bí àjàkálẹ̀ àrùn yí ṣe bẹ̀rẹ̀wọn kọ́kọ́ kéfin sí àrùn yí ní ọdún 1988, nígbà tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Malaysia, tí wọ́n sì amúnipamọ́ rẹ̀ ní ọdún 1999.. | wikipedia | yo |
.Àwọn àmì tí a fi lè mọ ẹni tí ó bá ní àrùn nípha lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́rìnlá tí aláìsàn bá ti lùgbàdì àrùn yí ni yóò ma bẹ̀rẹ̀ sí ní àìsàn ibà, orí- fífọ́, iṣẹ́ iyè méjì àti ṣíṣe ségesège ọpọlọ aláìsàn náà.. | wikipedia | yo |
Àwọn àmì yí lè sún síwájú kí ó sì di ara wíwú, tí ó sì lè fa kí ọpọlọ ẹni náà ó èpò.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ṣàánú náà tún le má kojú ìṣòro níbi ọ̀rọ̀ sísọ, àti àwọ̀ ibi kọ́lọ́fín ara.. | wikipedia | yo |
Àwọn aláìsàn tí wọ́n ní kòkòrò àrùn nìpha tí wọn kò lè má kanlẹ̀ ni wọ́n ní àǹfàní àti kó àrùn náà bá èlò mìíràn kía kía.Àwọn ẹ̀wù rẹàwọn òṣìṣẹ́ ilé ìwòsàn ni wọ́n ní wà ní ipò ewu jùlọ nítorí wípé àwọn ni wọ́n ń ṣètọ́jú àwọn aláìsàn fúndi èyí, ó ṣeé ṣe kí wọ́n tètè kó àrùn yí lára àwọn aláìsàn tí wọ́n ń tọ́jú.dídẹ́kun àjàkálẹ̀ àrùn ìdẹ́kun àjàkálẹ̀ àrùn nipha ni ó ṣe pàtàkì jùlọ nígbà tí kò tíì sí oògùn tí a lè fi dẹ́kun àrùn náà.. | wikipedia | yo |
Láti ṣe èyí, a gbọ́dọ̀ yálà fún jíjẹ àwọn èso èyíkéyí tí ẹyẹ bá ti jẹ, kí a yẹra fún sísúnmọ́ àwọn ẹlẹ́dẹ̀ àti lílọ sí ayé tí àrùn yí bá ti wà.. | wikipedia | yo |
Kíkó àwọn ohun jíjẹ sínú àpò ìpamọ́ tí ó lè dáàbò bo àwọn ohun jíjẹ wá.. | wikipedia | yo |
Ṣíṣe ìfílé nípa àjàkálẹ̀ àrùn yí kí a lè dẹ́kun ìtànkálẹ̀ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
tàbí Patrick Sehubo Koshoni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1943 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kìíní ọdún 2020 (April 17, 1943- 25 January, 2020) jẹ́ ajagun-fẹ́ynti orí omi Nigerian Navy Vice Admiral, Ọ̀gágun yányán Chief of Naval Staff àti Mínísítà-àná fún Ìlera nígbà ìṣèjọba ológun Ààrẹ Muhammadu Buhari.. | wikipedia | yo |
nígbà ìṣèjoba rẹ gẹ́gẹ́ bí Mínísítà-àná fún ètò ìlera, ó gbìyànjú láti ṣe ìdásẹ̀lé ètò Máàdámidó lórí ìlera láìsí owó ṣíṣàn kalẹ̀̀ nítọ́kasí ▪ Ológun ológun ará Nàìjíríààwọn ará Nàìjíríààwọn Ọjọ́lẹlọ́ ní 2020.. | wikipedia | yo |
Máàdámidódòfo jẹ́ ètò láti dá ààbò bo òfò owó tàbí dúkìá.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ètò láti máa ṣòfò owó dúkìá tí ìjàmbá àìròtẹ́lẹ̀ bá dé sí ni.. | wikipedia | yo |
Ènìyàn lè ṣètò dámidámidódòfo lórí ẹ̀mí, dúkìá tàbí ìleraàwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ orúkọ àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù jẹun lórílẹ̀-èdè Naijiriaabìà come—20 warriors f.C.Abiola babẹsabs f.C.Àbújá f.C.A Lagoda United f.C.C.Por United f.C.Akwa starlets fça United f.C.1.Anambra Pillars f.1.Anambra United f.Àpà United FCb8C f.3.0.17 United f.C.BCc Lions Insurance f.C.1 Boys f.C.S-6 United f.C.450 Knights f.fCC.3.D.D United football Club of Lagos Ros-crown f.Ncy.Ni FC of Ebonnyí stated.S United FCs FCta FC. | wikipedia | yo |
Ifelle1j United Stars f.C.SmmFM FCMighty jẹts f.C.My People FCdimila F.cnna Ackets f.C.Wáwá United f.ne.ne City f.450te Lagos Bank Nigeria Bank f.Niger ↑ TorNA.3 NA.3 Navco D.1] Oun.1] Judge football ríranbo boys f.Yàrá f.4 f.4 f.17.org f.450. Rols.S S[ei F.Mo f·vsing Stars &ei.S lọdọ f.S.S.S.S.4 f.4] Stars Stars SC United. | wikipedia | yo |
Arv]]wWarri Wolves f.C.Westside f.C.Wiki tourists f.C.Wocade United f.C.kódàkari Babes f[Zą FC of Bauchizam United f.C.C... | wikipedia | yo |
Ábìà warriors football Club jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jẹun lórílẹ̀ ède Nàìjíríà tí wọ́n wà ní ìlú Umuahia, ní Ìpínlẹ̀ Ábíá.Lọ́dún 2005 sí ọdún 2010, “Orji Uzor Kalu FC" ní orúkọ tí wọ́n ń jẹ́.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe èyí láti bọlá fún gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá nígbà náà Orji Uzor Kalu fún ìrànlọ́wọ́ àti akitiyan rẹ̀ tí wọ́n fi gba igbega sí ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù agbabuta àgbà ti Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n padà sí orúkọ wọn Ana lọ́dún 2010.Wọ́n ní ìga sí ìdíje agbábọ́ọ̀lù àgbà ti Nàìjíríà fún ìgbà àkọ́kọ́ lọ́dún 2013 lẹ́yìn tí wọ́n pegede nínú ikọ̀ adije agbabuta ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá kékeré.àwọn ìtọ́aìjíríà.. | wikipedia | yo |
Abiola Babes je iko egbe agbaboolu afẹsẹgba jẹun nigba kan ri, ni ilu Abeokuta lorilẹ ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Àgbà Òṣèlú, Olóògbé Shosho Moshood k Abiola ni ó ni ín.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gba igbega si idije agbabuta bọọlu afẹsẹgba ti orilẹ edè Naijiria lọ́dún 1984.Lọ́dún 2000, àtúnse dé bá ìkọ́ ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba naa, ṣugbọn wọn gbe ahan le wọn lọ́dún 2001 nitori iṣoro àìlọ́wọ̀.. | wikipedia | yo |
Their Last Game Was in the 2001 Challenge Cup Against nipost FC.Àwọn àṣeyọríolubori ninu idije ipele keji lọ́dún 1983(Nigeria 2nd Division Champion1983) olubori ninu idije Ife ẹ̀yẹ ti fa ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 1985 àti 1987.. | wikipedia | yo |
Ti àpèjá re n Abubakar Bukola Saraki FC jẹ iko ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba ti o fìkàlẹ̀ si Ilu [[Ìlọrin] lórílẹ̀-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gba igbega si idije agbabuta bọọlu afẹsẹgba ti orilẹ edè Naijiria sáà idije ti 2009–2010.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gba ìdíje àgbàbuta bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá àkọ́kọ́ ti Nàìjíríà ní Ìlú Ọ̀fà àti Bauchi nígbà tí àkọ́lé ń lọ lọ́wọ́ lórí gbọngan ìdárayá ti ìpínlẹ̀ Kwara Kwara State Stadium.. | wikipedia | yo |
Di iko egbe agbaboolu afẹsẹgba ti kii se ti ijoba ipinle kankan.lodun 2011 ni won paro oruko iko egbe agbaboolu afẹsẹgba yii kuro ni Bukola Babes si Abs (Abubakar Bukola Saraki) FC.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Abuja FC jẹ iko ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba-jẹun lorilẹ ede Naijiria, ti o n dije ni abala idije Nigeria Nationwide League.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dá ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí sílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kano, kí wọ́n tó darí rẹ̀ sí olú ìlú Nàìjíríà, Abuja.. | wikipedia | yo |
Wọ́n maa ń lo pápá ìserè Old parade Ground gẹ́gẹ́ bí ìdágan ìdíje NÍLẸ̀ WỌN.ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀ èdè Faransé kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Luc Lagọ́cheche ló dá iko ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí sílẹ̀ LỌ́DÚN 1998 nílé ẹ̀kọ́ èdè Faransé ní ìlú Kano.. | wikipedia | yo |
Leyin opolopo aseyori iko egbe agbaboolu afẹsẹgba yii ni abala awon idije agbabuta kéréje, Abuja FC gba igbega si abala idije to ga.. | wikipedia | yo |
Buffalo FC dèrò olú ìlú Nàìjíríà, Abuja lọ́dún 2006,wọ́n sìn yí orúkọ rẹ̀ padà sí Abuja FC, lẹ́yìn tí Ilé Iṣẹ́ Ìjọba Àpapọ̀ tí ó n gbógun ti ìwà ìkówọ̀ jẹ́ EFCC bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe onígbọ̀wọ́ fún wọn.. | wikipedia | yo |
Awon wonyi ni atojo awon olu-ilu awon ipinle ni Naijirimeje itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ronke Odusanya tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta Oṣù karùn-ún Ọdún 1973 (3rd May 1973) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Film producer and Stage performer.Ìgbé-ayé àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀wọ́n bí Ronke ní ọjọ́ kẹta Oṣù karùn-ún Ọdún 1973, (3rd May 1973) ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Benedict Nursery & Primary School ati Federal Government Girls College, Àkúrẹ́.. | wikipedia | yo |
Ronke tún tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ ní onísẹ̀ Olabisi Onabanjo, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí nínú ìmọ̀ iṣẹ́ ìròyìn.Aáyán nínú iṣẹ́ MgbanRonke Odusanya bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, lẹ́yìn tí ó kàwé ìdu ẹ̀rí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fún un ní ÀFLAKY Ìdí Dmú gẹ́gẹ́ bí orúkọ ìnagijẹ lágbo àwọn òṣèré sinimá àgbéléwò lẹ́yìn tí ó kópa nínu sinimá àgbéléwò kan tí Fathia Balogun kọ, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "folúkẹ́" lọ́dún 2006.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, Ronke kópa nínú sinimá àgbéléwò kan ti Adebayo Salami, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ògá Bello kọ, tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ "kẹríkẹrì" | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2001 ni ó kọ́kọ́ kópa gẹ́gẹ́ bí òṣèré Nollywood, nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ "Baba ọlọ́gbà" | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ìgbà náà, ó ti kópa nínú ẹgbẹlẹmùkù sinimá àgbéléwò, lára wọn ni ''Jenifa níbi tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Becky, Twisted, àti a Girl's note, àti àwọn sinimá-àgbéléwò mìíràn.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 2017, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí òṣèrébìnrin tí ó dára jù gẹ́gẹ́ bi Olú-ẹ̀dá ìtàn nínu sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, fún ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ailasaraṣe.Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa Twisted (2007) Jenifa (2008) láróda ọjọ́ (2008) Àròyìn ṣoṣo (2009) áṣáṣy (iṣìnà) (2016) A Girl's Note (2016)Àṣàkẹ́ Onike Bread (2016)The Stun (2017)Ayọ̀ (2017) Obud (2017)túnṣe (2017) Gbé 2018) Agbara (2018) Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Roman Polanski (Ọjọ́ìbí ojo 18 Oṣù Kẹjọ, 1933) Olùdarí QFI Faranse.. | wikipedia | yo |
Solomon Olamikan Adeola ti oruko inagijẹ re n je yayi ni won bi ni ojo ojo osu ojo odun 1969 (August 10, 1969), je onimo isiro ati asofin-agba nile igbimo asofin orile ede Naijiria ti o n ṣoju apa iwo oorun ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
Ó ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-sofin orílẹ̀ ède Nàìjíríà kí ó tó di Sineto.. | wikipedia | yo |
O je omo egbe Association of Accounting TechìdaríOlùràpadà (AAB).Awon itọkasiawon oloselu ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Joaquin Rafael Phoenix (; Ne Bottom; tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwàá ọdún 1984 (October 28, 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti olóòtú ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkàó ti gba ẹgbẹlẹmùkù Àmin ẹ̀yẹ nínú iṣẹ́ rẹ̀, pàápàá jùlọ Àmin ẹ̀yẹ BAFTA Award, a Grammy Award, Golden Globe Awards méjì, Screen Actors Guild Award, wọ́n sin yàn án fún Àmín ẹ̀yẹ Academy Awards nígbà mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Phoenix bẹrẹ iṣẹ osere sinima agbelewo lori ero tẹjade pelu awon egbon re, River ati Summer.. | wikipedia | yo |
Ipa gboogi akọkọ rẹ gege bi oṣere sinima ni ninu sinima SpaceCamp lodun (1986).. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó ṣe fẹ́ẹ́rẹ́, ó tún lọ ṣe ìyípadà sí orúkọ àbísọ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó sin gba lámèyítọ́ tó dárà nínu sinimá aláwàdà rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ tó die for lọ́dún (1995) àti sinimá mìíràn tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Quills lọ́dún (2000).. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbájúmọ́ sí nígbà tí ó kópa gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà ìtàn tí wọ́n pè ní Commodus nínú sinimá tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Gimiator Lọ́dún (2000), ó gba Àmin ẹ̀yẹ Academy Award for Best Supporting Actor fún sinimá yìí.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà wọ́n yàn án fún Àmín ẹ̀yẹ Best Actor fún ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn olórin Johnny cash nínú Walk The Line lọ́dún (2005), ọ̀mùtí ajagun fẹ̀hìntì nínú sinimá The Master lọ́dún (2012), nínú èyí tí ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ ti Volpi Cup for Best Actor, àti The Title Character nì Joker lọ́dún (2019).. | wikipedia | yo |
Àwọn fíìmù rẹ̀ mìíràn ni; Signs (2002) àti The Village (2004), gbajúmọ̀ sinimá ni Hotel Rwanda lọ́dún (2004), sinimá olólùfẹ́ her lọ́dún (2013), Inhént Vice lọ́dún (2014), àti You Were Never Polytechnic Here lọ́dún (2017), èyí tí ó fi gba àmìn ẹ̀yẹ Cannes Film Festival Award for Best Actor.Phoenix máa ń ṣiṣẹ́ olóòtú, olùdarí sinimá àgbéléwò àti tẹlifísàn.. | wikipedia | yo |
O sin gba amin eye Grammy Award for Best Gana Antils for Visual lori Walk The Line.Àwọn ìtọ́kasíàwọn oṣere ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Èyí ni àtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkà nípa bí wọ́n ṣe pọ̀ tó níye, a kó èyí sílẹ̀ nípa lílo ìwòye iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìtọ́kasí ètò ìkànìyàn tí wọ́n ṣe lẹ́yìn lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Láìsí àní-àní, ilẹ̀ Áfíríkà sì ni ilẹ̀ tí ó ń dàgbà jùlọ níye ènìyàn ní gbogbo àgbáyé lẹ́yìn ilẹ̀ Asia.. | wikipedia | yo |
ìdá ọgọ́ta (60%) àwọn ènìyàn Áfíríkà ni wọ́n wà ní ọmọ ọjọ́ orí mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n tàbí kéré sí iye ọjọ́ ORÍ YẸN SÍ ỌJỌ́ ORÍ WỌN, èyí WA mú kí ṣíṣe ate ìsókèsókè Iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan dá le bí ètò ìṣèjọba àti Ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀-ajé ṣe ṣe pàtàkì tó.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àrùn kòkòrò jẹjẹrẹ jẹ́ àkójọpọ̀ àrùn tí ó kódà jẹ́ pọ̀ tí wọ́n sì ń dàgbà lọ́nà àtio nínú apá ibìkan nínú ara tí ó sì lánfàní láti tàn ká gbogbo oríkeríke ará tó kù… | wikipedia | yo |
àrùn jẹjẹrẹ yàtọ̀ sí BeniGN tumor, èyí tí kìí tàn ká ara.Bí a ṣe le mọ̀ wípé a ní àrùn jẹjẹrẹlara àwọn ọ̀nà tí a lè gbà mọ̀ wípé a ní àrùn kòkòrò yí ni kí apá ibi kan ó wú, kí ó pupa, kí ó sì le gbagidi, kí ẹ̀jẹ̀ ó má ya láì dúró, ìkọ́ ẹ̀gbẹ́, kí ènìyàn ó dé de má rẹ̀ láì nìdí àti kí ìyàtọ̀ ó dé bá bí ènìyàn ṣe ń ṣegbọnsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Awon ti a ka sile yi n tọka si nini arun kokojẹjẹrẹ, awon ami miiran naa tun le sọni yano si awon wọnyi.. | wikipedia | yo |
Over 100 types of cancers affect humans.Àwọn ohun t í ó ń fa àrùn kòkòrò jẹjẹrẹlara àwọn ohun tí ó ń fà ní mímú tobacco ni ó ń fa ikú tí ó èdè méjìlélógún nínú ẹ̀dà ọgọrun tí ó ń pa àwọn ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun tí ó ń sokunfa àrùn yí mìíràn ní ìka àìsàn mìíràn.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Lábẹ́ yìí àtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè nílẹ̀ àsíá nípa agbègbè wọn ní àtọ̀ álúfábẹ́ẹ̀tì.. | wikipedia | yo |
Àwọn wọ̀nyí ni a fi Àmin ìràwọ̀ ( ) yìí fi ṣàfihàn wọn.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Itun sọmọ bibi ni a le pe ni ilana Ọlọrun ti o ni ṣe pẹlu bi a ṣe le pinu lori iye ọmọ ti o ba wuni lati bi, lai ko si ìjẹ́ni nipa lori bi a se le fi asiko si aarin àwọn ọmọ ti a fẹ bi naa lona ti ko ni pa wa lara, yálà ni oogun lilo, ìgbé ayé ti o dara ninu àwùjọ fun ẹni kọọkan ni ati bẹẹ bẹẹ lọ .. | wikipedia | yo |
Ètò ìlànà ìfẹ̀tọ́ sọọmọ bibi tún dá lórí pípinu lórí bóyá ki obinrin ó me iye ọmọ ti ó bá fẹ́ bi ki ó si fi àsìkò si aarin wọn, tàbi ki ó pinu la ma tilẹ̀ dábàá àti bímọ kankan rara láyé rẹ, tàbi ki ó fi àyè silẹ̀ fún ọmọ bibi ninú ònkà ọjọ́ ayé rẹ ti ó fẹ́ fi bímọ.. | wikipedia | yo |
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ṣáájú kí obìnrin tó lóyún,àti àbójútó oyún.Gbọ́gbọ́ ọ̀rọ̀ nípa ìfètò sọ́mọ bíbíoyún ṣíṣẹ́ kìí ṣe dandan la lára ìlànà ìfètò sọ́mọ bíbí, lóotọ́, oògùn lílo àti àwọn ìlànà míràn tí a ti là kalẹ̀ ma ń dènà kí obìnrin ṣẹ́yún.Family Planning, as defined by the United Nations and the World Health Organization, Encompasses services leading up to Conception.. | wikipedia | yo |
Abortion is not considered a trivinent of family planning, pupọ ninu àwọn obinrin tí wọn ń lo òògùn láti fi de na oyún ni wọ́n ń ṣe ìfètò sọ́mọ bíbí.. | wikipedia | yo |
Àwọn bí ìràwọ̀, ọ̀dọ́mọGu bìnrin tí kò tíì làkò, àwọn ìkòko- tí wọ́n fẹ́ ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ lọ́Eo kí kí tó bímọ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Rọ́bà ìdáàbòbò jẹ́ ohun èlò kan tí a lè fi dènà oyún abadi, aisan, arun àti ìfara-káṣà tí ó lè ń ṣàkóbá fún àgọ́ ara okùnrin tàbí obìnrin nípasẹ̀ ìbálòpọ̀ lásìkò tí a bá ń ní ìbò lọ́wọ́ tàbí nílé ìbálòpọ̀ ohun.. | wikipedia | yo |
To̩kùnrin tobìnrin ni wọ́n ní rọ́bà ìdáàbòbò tiwọn.Àwọn ẹ̀rí Máàjémi nìṣó rẹ̀ìwádí fi yéni wípé ó kéré tán ìdá méjì obìnrin ni wọ́n ma ń lóyún lọ́dún, nígbà tí ìdáná méjìdínlógún %18 l ó ma ń lóyún lọ́dún nígbà tí ọkọ wọn tàbí olólùfẹ́ wọn bá lo rọ́bà ìdáàbòbò.. | wikipedia | yo |
With obìnrinàwọn use the rate of Pregnancy is 18% per-year.. | wikipedia | yo |
Lílo Los Ìdáàbòbò ti mú àdínkù bá kíkó àrùn àtọ̀sí, àrùn Éèdì àti àwọn mìíràn jọjọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ láti ẹnu, èyí túmọ̀ sí wípé akọ tàbí ọkùnrin yóò ki nkan ọmọkùnrin rẹ bọ ẹnu olólùfẹ́ rẹ láti ní àṣepọ̀. | wikipedia | yo |
Kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ nípa lílo àwọn ohun èlò ìbálòpọ̀ tí wọ́n gbé bí nkan ọmọkùnrin.Àmọ́ irúfẹ́ àwọn ọ̀nà ìbálòpọ̀ tí a kà sílẹ̀ yí kò bá ìlànà àṣà Yorùbá mu yàtọ̀ sí kí a bára ẹni lò pọ̀ láti ojú ara, èyí tí ó tọ̀nà jùlọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
fùrọ̀ túmọ̀ sí ihò róbótó ti jásinu tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ àpò-àjẹsí ẹranko tabi tènìyàn, tí ó sì já sóde tí ó ń ṣiṣẹ́ fún yíya tabi ṣíṣe ìgbàonṣẹṣẹ àwọn ohun burúkú tí kò wúlò fún ara mọ́ tó wà ní àgbào ara.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Jide Ogunsanya ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun osù kẹrin jẹ́ oníṣòwò, ìlú bá ní tajà, aláṣẹ àti olùdarí búlọ́ọ̀gì ọgbọ́n ti orí ẹ̀rọ alátagbà Níb i tí ó ti ń dá àwọn ẹni nípa bí a ṣe lé lọ́wọ́-jèrè.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Gozel Green jẹ́ ilé iṣẹ́ ìránṣo ti àwọn obìnrin ìgbàlódé ti àwọn ibeji ti oruko won n je Sylvia Enekwe àti Olivia ọkọji da sile ni odun 2012, ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |