cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Oríṣi orúkọ kẹ́ta ni àwọn oríkì ṣókí já sí gan-an, ṣùgbọ́n ó wọ́pọ̀ ká pààlà láàrín orúkọ gidi àti oríkì..
wikipedia
yo
Ìdí èyí ni pé ọ̀rọ̀ Ajuwe ni oríkì ṣókí, ọ̀rọ̀ t'ó júwe ìwà àti ìṣe àti ara olóríKí náà..
wikipedia
yo
Arun erankorona odun 2019 (tabi ni ede Geesi bii coronavirus disease 2019, COVID-19) je arun àkóràn kan ti ẹran àròlu aisan imin oloro gbigboro, ẹran korona iru 2 (SARS-CoV-2) n mu wa..
wikipedia
yo
Àrùn náà kọ́kọ́ jẹ́ DÍDÁmọ́ ní December 2019 ní Wuhan, ní China, tó si ti ran ka gbogbo àgbáyé lati igba náà pẹ̀lú ìjàkárin-àrùn kaakiri erankorona ọdún 2019-2020..
wikipedia
yo
Nínú àwọn àmì-àìsàn rẹ̀ tó wọ́pọ̀ ni ibà, ikọ̀, àti àìlèmin balẹ̀..
wikipedia
yo
Awon ami aisan miran tun le je ìrora, híhá kélébé, igbe olomi, ìkanra ona-ọ̀fun, AHábákúkù Oorun, ati Ìrora ikun..
wikipedia
yo
bọ̀bjẹ́ pé ọ̀pọ̀ aláìsàn àrùn yi ni àmì-àìsàn tó lọ́wọ̀rọ, àwọn míràn le ní ẹran Ẹdó àti ìkùnà pátápátá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìra-ara..
wikipedia
yo
Titi di ojo , iye awon alaisan COVID-19 ti a mo lagbaye je , iye awon alaisi je deaths.Iye awon ti ara won ti ya je .Awon itọkasi drink green tea, take vitamin C, turmeric, IGIGger and elderberry, eat oranges, fruits and vegetables..
wikipedia
yo
Àwọn alówó funfun wá láti òkè òkun láti wá wúrà yìí eré yìí bákan náà jẹ́jẹ kí a mọ iye owó ti wúrà yí gbẹwọ̀n tí ó jẹ́ 1billion US Dollar.Ẹnìkan ní ìdílé kọ̀ọ̀kan ni ó létò láti mọ ibi tí wúrà yìí wà..
wikipedia
yo
Nínú eré yìí bákan náà arákùnrin yìí gbìyànjú láti mú àfojúsùn rẹ̀ wá sí ìmúṣẹ láti rí wúrà náà..
wikipedia
yo
wọ́n sì jẹ́ kí a mọ̀ wípé ọgbà ẹ̀wọ̀n ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ni wọ́n ní wúrà yíi wà..
wikipedia
yo
Nítorí àti gbé wúrà yìí, arákùnrin yìí ní láti dáràn síra rẹ lọ́run..
wikipedia
yo
Ọ̀nà tí ó gbà gbé wúrà yìí jáde ní láti pàdí àpòpọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ó kù tí ó sì tàn wọ́n wípé òun yóò gbé ilé tí a mọ̀ sí túnNel láti jẹ́ kí wọ́n jáde..
wikipedia
yo
Eyi fun àwọn ẹlẹ́wọ̀n tókù lati darapọ mọ lai mọ wipe lati gbe wúrà naa jade ni o se sọ fun wọn wipe ki wọn gbe ilẹ̀..
wikipedia
yo
Kámá fa ọ̀rọ̀ gùn, arakunrin yìí fi tó ọ̀gá ẹlẹ́wọ̀n létí nípa ohun tí ó gbé wá sílé ẹ̀wọ̀n, ó fi ọ̀rọ̀ náà tó ọ̀gbẹ́ni náà létí ẹni tí a mọ̀ sí Ali Baba..
wikipedia
yo
Arakunrin yìí náà darapọ̀ mọ́ láti jẹ́ kí iṣẹ́ náà jẹ̀ẹ́ àṣeyọrí..
wikipedia
yo
Arákùnrin ṣe àṣeyọrí nínú iṣẹ́ náà ṣùgbọ́n ó tún rí ìdojúkọ láti ọ̀dọ̀ ìjọba nípa wúrà yìí ṣùgbọ́n ó kọ̀ jálẹ̀ láti gbé sílẹ̀ fún ìjọba.Lẹ́yìn ère yìí arákùnrin yìí àti àwọn tí wọ́n jọ lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ yìí di ènìyàn ńlá…
wikipedia
yo
Hadja Saran Dakoko Kaba (ti a bi ni ọdun 1945) jẹ aladun obinrin ti ilu Guinea, Akowe akoko ti oludari gbogbogbo ti Mano River Union ati oludije Alakoso 2010 ni idibo gbogbogbo Guinea ni ọdun 2010 2010 .ìgbésíayé Hadja Saranba Kaba ni a bi ni 1945 ni Coyah, Guinea..
wikipedia
yo
O ṣe ikẹkọ bi ile elegbogi ni Leipzig ati Halle ni Germany laarin ọdun 1966 si 1979..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1970, o pada si Guinea nibiti o ti ṣe ikẹkọ ni Ẹkọ Ile-iwosan ti Hadja Mafory Bangoura ati Lẹhinaa darapọ mọ Pharmaguinée nibiti o dide lati di Igbakeji Oludari ti Orilẹ-ede okeere ni Ile-iṣẹ fun Iṣowo Ajeji..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1996 o di minisita awujo awujo ati igbega ti awon obinrin ati awon omode.idibo alakoso ni odun 2010, o je obinrin kan soso ninu awon oludije fun alakoso ijoba Guinea .O River Union laarin osu Kesan odun 2011 ati odun 2017, o je Akowe Gbogbogbo ti ìṣọdọmọ odo mano ati oludasile ti Netist obinrin ti mano River Union for Peace (Ref) okan ninu awon ẹya pataki julo ti awujo ara ilu Afrika Afrika eyiti o se iranlọwọ pupo si ipinnu naa ti awon ariyanjiyan pupo ni agbegbe agbegbe ati si ominira ti awon obinrin Afrika ati pe o gba aami-eto omo-eniyan ti un ni 2003 .Awon itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1945 Alààyè Amuniji ara Guinea..
wikipedia
yo
Islam Bibi ( ; Ni ọdun 1974 - 4 Osu Karun ọdun 2013) jẹ ọlọpa obinrin kan ni Afiganisitani ati pe o tun jẹ aṣáájú-ọna ninu ija fun abo ..
wikipedia
yo
O jẹ arabinrin ọlọpa ti o ga julọ ni akoko iku rẹ ni Afiganisitani o si ṣe awọn iṣiṣẹ si awọn Talibans ..
wikipedia
yo
O gba awọn irokeke ikuwo si pa on ni osu keje ijo mẹrin, 2013 .igbesi ayewon bi bibi ni agbegbe Kunkuz ni ọdun 1974 ..
wikipedia
yo
O jẹ arabinrin ọlọpa ti o ga julọ ni igba yẹn ati gba ọpọlọpọ awọn irokeke iku ti o fi ewu rẹ si ..
wikipedia
yo
O mu ọkan ninu awọn ẹgbẹ ọlọpa obinrin ti o tobi julọ ni Afiganisitani ti o lepa awọn Taliban, wiwa fun awọn olukọ pipa ara ẹni ti o jẹ idiyele ni BurAge ati pe wọn ni akọkọ lati fọ sinu ile eyikeyi lakoko iwadii ni awọn agbegbe awọn obinrin nibiti a ko gba laaye awọn ọlọpa ọkunrin .Iku wọn yin ibon fun bibi nigbati o jade kuro ni ile rẹ ni owurọ ti Oṣu Keje ọjọ kẹrin, ọdun 2013ni adugbo Lakarkar Gah, Olu-Ilu ti Heland ..
wikipedia
yo
O ni omo mefa.Awon itọkasi awon ojoalaisi ni 2013awon Ọjọ́ìbí ni 1974..
wikipedia
yo
Lucka Kajfefe Bogaj (tí a bí ní ọdún 1957) jẹ́ onímọ-jinlẹ ará ìlú SLOVENIA àti olùjade olúborí kí Nobel ní 2007..
wikipedia
yo
O pari ni ọdun 1980 lati Ljubljana Faculty of Natural Sciences and Techgerolog ati gba iwe-ẹkọ dokita lati olukọ imọ-ẹrọ .Iṣẹ ralé o jẹ awadi ati alamọdaju ni Ilup of Ljubljana ..
wikipedia
yo
Bogaj jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Igbimọ Ijoba Iyipada ni Geneva .Awon idanimo ni odun 2008, alakoso ijoba ìkọ̀sẹ̀aníà lehinaa, danilo Turk, fun ni ebun fun awon ise takuntakun re.Awon itọkasi awon eniyan alààyẹ̀..
wikipedia
yo
Nelsa Cardoso (ti a bi ni ọdun 1970) jẹ alamọdaju ara ilu Brazil ati olukọ .itan ìgbésíayé ti a bi ni ọdun 1970 , ni Ilu Brazil, o ni ìmọ̀ ni Sciences lati Ile ẹkọ Universiti ni Ilu Brazil..
wikipedia
yo
Interpretaco palẹ̀oam Mo- pa popamati na Reconstrustru2 da palẹ̀ekarùnÀlàáfíà..
wikipedia
yo
Uma Dickgbangba] Ferkojú no ẹòòrìṣà da ilha King George, Peninsula bùáyàêutica..
wikipedia
yo
Detido das Cuticu Fsse da Flora do palẹ̀ola Cakoko Owole, CAimiO, Go..
wikipedia
yo
Xâ SPPpp - Insha Brasileiro de Yâdun Yoloa e PAlin..
wikipedia
yo
Soṣọ de diatoceasas fosse como Evidencia de morte em vitimas de Arokogasia domesticos..
wikipedia
yo
Igbeyawo jẹ isorisi laarin okunrin ati obinrin lati di ẹyọkan, lati jo maa gbe po gege bi ọkọ ati aya.Àṣà igbeyawo ni ile Yoruba se koko, awon ojo wabo, won ni “Iyawo dun un gbe, ọmọ dun un ko jade”
wikipedia
yo
Igbeyawo jẹ aṣa to se pataki ju ọmọ bibi lo paapaa julọ laye ode oni .eni ti o ba ti to lati gbeyawo, ti o ko ti ko ṣe bẹ, awọn babańlá wa ma n ki ẹni naa pe "awa ma gbeyawo, Kenàjàgà àtàrí bi ẹrùu fìlà” won tun ma n pe ni “Ògòǹgò bi agba a tọ Baale ile ma gbe iyawo..
wikipedia
yo
Orísirísi ọ̀nà ni a le gbà láti gbé ìyàwó ní èyí tí kò yọ ọ̀nà tipátipá náà sílẹ̀..
wikipedia
yo
Yorùbá kì í fi ipá l'ọwọ́, a kì í fi agbára bí ọmọ, ṣùgbọ́n wọ́n a máa fi ipá gbé ìyàwó..
wikipedia
yo
Bi o ba ti tó àkókò fun ọlọ́mọkùnrin lati gbéyàwó, ti o kọ lati ṣe bẹ, àwọn babańlá wa ma ń kí ẹni náà pé "Àwa mà gbéyàwó, Kenàjàgà àtàrí bí ẹrùu fìlà” wọ́n tún ma ń pè ní “Ògòǹgò bí àgbà á tọ baálé ilé má gbé ìyàwó.Oríṣiríṣi ìgbéyàwó asánté asán yí lé wáyé nígbàtí ọkọ ìyàwó ìyàwó bá ń fura wí pé àwọn òbí ọmọbìrin náà fẹ́ fi ọbẹ̀ ẹ̀yìn jẹ òun n'iṣu, tàbí tí ó bá rí i pé ojú ọmọbìrin náà ò gbé ibì kan..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ ìgbéyàwó bayi máa ń wáyé nígbàtí ọkọ-iyawo yí bá lọ jí ìyàwó àfẹ́sọ́nà rẹ̀ gbé yálà nígbà tí ọmọbìrin náà bá ń ti ọ̀nà.Igbeyawo pàdémi nidii máa ń wáyé nígbàtí àwọn olólùfẹ́ meji bá ń fẹ́ ara wọn ṣùgbọ́n ti àwọn òbi wọn mejeeji kò lówó sí tabi ti wọn kò fẹ́ kí wọ́n fẹ́ ara wọn..
wikipedia
yo
Báyìí ni àwọn ọkọ àti ìyàwó yóò bá sálọ sí ìlú mìíràn láti lọ bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò ayé wọn láìsí ìyọ̀ǹda àwọn òbí wọn níbẹ̀ pé kí wọ́n fẹ́ ara wọn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọdún díẹ̀ tí wọ́n bá ti sálọ , tí wọ́n sì ti bímọ méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ wọ́n lè pinnu àti padà wá sí ìlú wọn.Igbeyawo gbàmí- o- rámìèyí ní irúfẹ́ igbeyawo ti o ṣábà máa ń waye láàrin oníṣègùn tabi babaláwo ati ọmọbirin..
wikipedia
yo
Eyi maa n sele nigbati ara ọmọbirin naa ko ba ya , ti aisan tabi egbò nla kan ba kọlùú ti won si ti nawo-nára sugbon ti won o rọ́jútu aisan naa, ti wọn wa gbe lọ si ọdọ babaláwo tabi onisegun kan, ti won si se ileri fun onisegun naa pe ti o ba le wo ọmọbirin naa san, oun ni ọmọbirin naa yoo fẹ nigba ti ara rẹ ba ya.Igbeyawo oLóríawọn agba bo wọn ni won ni babaláwo ni n ṣ'oko àbíkú..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ igbéyàwó yí ma n waye nigbati wọn ba wọ àkọsẹrin ọmọbìrin ti ifa si sọ fún wọn pe orisa funfun ni ọkọ rẹ..
wikipedia
yo
Awon obi omo yii o wa lo gbe omo naa fun awon ajoàh tabi odo Baba..
wikipedia
yo
Lọ́nà kejì ẹ̀wẹ̀, tí ọmọbìrin bá ti dàgbà tí ọkùnrin kankan lósì kò ẹnu ìfẹ́ sí rárá...
wikipedia
yo
Ti wọ́n bá lọ yẹ ifa wò, babaláwo lè sọ fún wọn pé ọmọbirin náà ti l'oko ati wipe orisa kan ni oko rẹ je.Tabiìgbéyàwó ibile ati igbeyawo ode-oni-igbesi ati ilana igbeyawo abinibi ile Yoruba ..
wikipedia
yo
Ìdílé mìíràn àwọn obìnrin wọn kìí gbé ilé ọkọ dalẹ̀, ìdílé mìíràn ìgbésí jíjẹ a máa rọ̀ wọ́n lọ́rùn, ìdílé mìíràn wọn kìí dàgbà, wọn yóò tún tẹ̀ síwájú láti ṣe ìwádìí irú ènìyàn tí ọmọbìrin náà jẹ́ bóyá àṣà ọmọ ni, bóyá oní kébékébé ni, lẹ́yìn èyí ni wọn yóò wá lọ béèrè lọ́wọ́ ifá gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́ri-ìpín tí kò leè purọ́ , gbogbo àṣírí ọjọ́ ọ̀la ìgbéyàwó náà ni yóò hàn kedere láti ọ̀dọ̀ ifá.3..
wikipedia
yo
Ọmọkùnrin yìí yóò wá san owó ìṣíhùn fún àwọn ẹbí ọmọbìnrin yìí kí ó tó lè máa bá ọmọbìnrin náà sọ̀rọ̀, owó náà jẹ́ òkè kan láyé àtijọ́wọn yóò sì fi obì àbàtà, ataare, àti orógbó sí owó ìṣíhùn náà.5..
wikipedia
yo
Àwọn òbí ọmọbìnrin yìí yóò dájọ́ fún àwọn ẹbí ọmọkùnrin pé kí wọ́n padà wá , ó lè jẹ́ lẹ́yìn ọjọ́ méje tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, àwọn ẹbí ọmọbìnrin yìí náà yóò lọ ṣe ìwádìí nípa irú ìdílé tí ọmọkùnrin náà ti jáde, irú ènìyàn tí òun fúnra rẹ̀ jẹ́, wọ́n yóò tẹ̀ síwájú láti ṣe ìwádìí lọ́wọ́ ifá bí ọjọ́ iwájú ìgbéyàwó náà yóò ṣe rí, tí ìwádìí wọn bá yọrí ṣiré, gbígbọ́ àti gbígbà tí àwọn òbí ọmọbìnrin gbà láti fi ọmọ wọn obìnrin yìí gẹ́gẹ́ bí aya ní àwọn Yorùbá ń pè ní Ìjọhen tàbí bàbá gbọ́ ìyá gbọ́.6..
wikipedia
yo
Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ tí ìyàwó yóó rẹ ilé ọkọ rẹ , lẹ́yìn tí o bá ti múra tán, yóò lọ dágbére fún àwọn òbi rẹ àti àwọn ẹbí, àkókò yìí ni ìyàwó yóó máa sun ẹkún ìyàwó láti fi dágbére , láti fi dúpẹ́ àti láti fi gba ire/àdúrà lẹ́nu àwọn òbí àti ẹbí rẹ, àwọn ọ̀rẹ́ rẹ yóò sì máa tẹ̀lé e bí o ti ń sun ẹkún-ìyàwó kiri wọn yóó máa rẹ̀ ẹ́ lẹ́kún..
wikipedia
yo
Àṣálẹ́ ni yóò tó darí padà sí ọ̀dọ̀ àwọn òbí rẹ̀, lẹ́yìn ìwúre bàbá yóò fa ìyàwó lé owó obìnrin tí ó jẹ́ àgbà nínú àwọn ẹbí ọkọ lọ́wọ́, àwọn ìyàwó-ilé àti àwọn ọ̀rẹ́ ìyàwó yóò fi ìlù àti orin tẹ̀lé e lọ sí ilé ọkọ rẹ̀.Ọkọ ìyàwó ti gbọdọ̀ kúro ni ilẹ̀ kí wọ́n tó mú ìyàwó rẹ̀ dé, èèwọ̀ ni ni ilẹ̀ Yorùbá ìyàwó kò gbọdọ̀ bá ọkọ rẹ̀ nílé ni alẹ́ ọjọ́ ìgbéyàwó wọn, lẹ́yìn tí wọ́n bá ti mú ìyàwó wọlé tán ni ọkọ ìyàwó yóò tó wọlé wá..
wikipedia
yo
Àwọn Ìyáálé ìyàwó yóò bu omi tútù sí ẹsẹ̀ ìyàwó tuntun lẹ́nu ọ̀nà àbáwọlé, ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá nípa èyí ni wípé kí ìyàwó lè fíbófi ṣe èrò wọlé ọkọ rẹ̀.Lẹ́yìn èyí wọn yóò dojú ìgbà gbígbé délẹ̀ kí ìyàwó tuntun fíbó ṣe fọ́ ọ, àwọn Yorùbá ni ìgbàgbọ́ pé iye ọ̀nà tí ìgbà yìí fọ́ sí ni iye ọmọ tí ìyàwó yóò bí, tí ó bá wùú Ó lè má bí tó bẹ́ẹ̀ tàbí kí ó bí jù bẹ́ẹ̀ lọ.8..8..
wikipedia
yo
Àwọn òbí ọkọ yóò títẹ́ aṣọ funfun sí orí ibùsùn nínú yàrá ọkọ ìyàwó láti fi gba ìbálé ìyàwó rẹ̀..
wikipedia
yo
Iyì ńlá ni fún àwọn òbí ìyàwó tí ọkọ rẹ̀ bá nílé, ó túmọ̀ sí wípé ọmọbìnrin náà kò tíì mọ ọkùnrin rí..
wikipedia
yo
Odidi àgbẹ̀ ẹmu tàbí odidi páálí ìṣáná,ìyàn àti ọbẹ̀ tí ó dára ni àwọn ẹbí ọkọ-ìyàwó yóò gbé lọ fún àwọn òbí ìyàwó Láàró kùtù ọjọ́ kejì láti fi dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn wípé odidi ni wọ́n bá ọmọ wọn , èyí ni oúnjẹ ìbálé, ìyàwó yóò tún gba ọwọ́ ìbálé tii ṣe òkè-méjì lọ́wọ́ ọkọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtìjú ati àbùkù ni fún iyawo tí ọkọ rẹ̀ kò b ànílé, ìlàjì àgbẹ̀ ẹmu tàbí ìlàjì páálí ìṣáná ni àwọn òbí ọkọ ìyàwó yóo fi ranṣẹ sí àwọn òbí iyawo tí ọkọ rẹ̀ kó b ànílé láti lè jẹ́ kí wọ́n mọ̀ wípé ọmọ wọn tí mo ọkùnrin rí.9..
wikipedia
yo
Ọjọ́ yìí náà ni yóò jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ tí yóò dáná oúnjẹ fún ọkọ rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka síàṣà Yorùbá..
wikipedia
yo
ọ̀fun (), tí a tún mọ̀ sí òǹfà oúnjẹ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà ara inú tí ó dàbí okùn oníhò tí ó ń ṣiṣẹ́ gbígbẹ oúnjẹ láti ẹnu lọ sí inú ikùn tí ó wà ní ara gbogbo ohun abẹ̀mí tí ó bá tí ń jẹ tàbí mú ohun kóhun..
wikipedia
yo
ọ̀fun yí dà bí Ahoho tí ó gùn ní ìwọ̀n mẹẹdọgbọn lára àgbàlagbà eniyan tí ó rọra gba ẹ̀yìn òkun ọ̀hún, ọkàn ati iṣan àtẹ̀gùn tabi èémí kọjá, tí ó sì fẹnu sọlẹ̀ sí inú ikùn..
wikipedia
yo
Lásìkò tí a bá ń gbé oúnjẹ mì lọ́wọ́, gògòńgò yóò dí lọ́wọ́ ẹ̀yin kí a má ba le gbé oúnjẹ parí.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ni ojo ketadinlogbon osu keji odun 2020 ni won koko kede lati fidi isele akoko nipa ajakale arun COVID-19 mule ni ile Naijiria, nigba ti won se ayewo fun omo orile-de Italy kan ni ilu Eko ti ayewo si fi han wipe o ni arun y ni eyi ti SARS-t Ov-2 n fa.Ni ojo kesan an osu keta odun 2020, ni won kede isele eleekeji lori arun COVID-9 ni ewekoroko, n ipinle Ogun latipase omo orile ede Naijiria kan ti o ni ifarakanra pelu ara ilu Itali yi.Ìpìlẹ̀ ni ojo kejidinlogbon osu kini odun 2020, ni ijoba apapo ile Naijiria mu da gbogbo omo theorile ede Naijiria loju nipa imurasile ijoba lati mu ki amojuto ti o lagbara wa fun awon papa oko ofurufu nla maraarun lati se idiwo fun itankale arun COVID-19..
wikipedia
yo
Ijoba kede awon papa ọkọ ofurufu bi ti Enugu, Eko, Rivers, Kano ati ti olú Ilu Naijiria ni Abuja..
wikipedia
yo
Ile ise ti o nse isakoso didena arun ni ile Naijiria (Nigeria Centre for Disease Control) tun se ikede ni ojo kanna pe awon ti se agbende egbe ti yio ma ri si arun COVID-19 ati wipe awon ti setan lati dojuko isele ki isele ti o ba jẹyọ lori arun yi ni ile Naijiria..
wikipedia
yo
ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kíní ọdún 2020, lẹ́hìn ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 ti ń jà Kárdínlógójì Àgbáyé èyí tí ó ṣẹlẹ̀ ní, mainland, olú ìlú China àti ní àwọn orílẹ̀ èdè míràn ní àgbáyé, ní ó mú kí ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà se agbende ẹgbẹ́ Ìmúrasílẹ̀ fún Àrùn COVID-19 láti dojúkọ ìkọlù àrùn yí tí ó bá wa tàn kálẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ni ojo kanna igbimo ti o nri si ilera gbogbo orile ede ni agbaye (World Health Organisation) se akosile orile ede Naijiria pelu awon orile ede metala miran ni Afrika gege bi ibi ti o lewu ju fun itankale arun COVID-19.Ni ojo kerindinlogbon osu keji odun 2020, ara ilu Chinese kan se afihan ara re si ijoba ipinle Eko lori ifura pe ohun ti ko arun COVID-19..
wikipedia
yo
Wọ́n gbe ẹ lọ sí ilé iwosan ti Reddington (Reddington Hospital) fún ayewo..
wikipedia
yo
Wọ́n fi í sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì lẹ́hìn tí àyẹ̀wò sọ wípé kò ní àrùn yí.Àkójọpọ̀ àkọ́kọ́oṣù kejì ọdún 2020 ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, Nàìjíríà fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó múlẹ̀ nígbàtí ará ìlú Itali kan tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ní Nàìjíríà gba pápá ọkọ̀ òfúrufú ti Murtala Muhammed padà wọlédé láti Milan, Itali ní ọjọ́ keedọokegbon oṣù kejì..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n ni arákùnrin yí dùbúlẹ̀ aisan tí wọ́n sì gbé e lọ sí biọ̀sẹ̀bojú Faomolu ní Ìpínlẹ̀ Èkó fún iyasọtọ àti àyẹ̀wò.Oṣù Kẹta ọdún 2020 ní ọjọ́ kẹsàn oṣù kẹta ni wọ́n fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ kejì múlẹ̀ látipasẹ̀ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà kan ní Ewekoro, Ìpínlẹ̀ Ògùn, tí ó ní ifarakanra pẹ̀lú ará ìlú Ítálì.Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta, Nàìjíríà jẹrisi pé àyẹ̀wò tí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé kò sí àrùn Corona nínú àgọ́ ara okùnrin tí ìsẹ̀lẹ̀ kejì ṣẹlẹ̀ sí..
wikipedia
yo
Eniyan marun un gba ominira ni ile iwosan nigbati eniyan kan je alaisi..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ṣe ìkéde pé wọ́n dá ènìyàn márùn-ún sílẹ̀ ní ilé ìwòsàn tí ènìyàn méjì sì jẹ́ aláìsí..
wikipedia
yo
Nàìjíríà kéde pé àwọn ti fi kún àyẹ̀wò nípa ìpín àádọ́ta nínú ọgọ́rùn-ún (50%) pẹ̀lú 1,500 àyẹ̀wò àwọn ènìyàn fún ọjọ́ kan tí wọ́n sì ń yẹ àwọn tí ó tó 6000 ènìyàn wò àti wí pé wọ́n ti ní ibi àyẹ̀wò mọ́kànlá..
wikipedia
yo
àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun 3,852 ni ó ṣẹ́yọ ní oṣù Kẹwàá, èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ti ṣẹ́yọ láti ìgbátí àjàkálẹ̀ àrùn yí ti bẹ́ sílẹ̀ di 62,853..
wikipedia
yo
Iye awon ti o ti je alaisi lo soke lati mejilelogbon si 1,144..
wikipedia
yo
Awon alaisan ti won n gba itoju lowolowo je 3,034 ni opin osu yi..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun mẹ́rìnlélógún ni ó tún ṣẹ́yọ ní oṣù kẹwàá, èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye ńàwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ti fi dì ẹ́ múlẹ̀ di 1,220..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti won ti gba iwosan lo soke si 1137, nigba ti awon alaisan merinla n gba itoju lowolowo ni opin osu ojo.osu Kọkànlá odun 2020 isele tuntun 4,704 ni o seyo ni osu kokanla, eyi ti o mu ki apapo iye awon isele arun korona ti o ti bujade di 67,ibikíbi..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti o n gba itoju lowolowo je 3,102 ni opin osu Kọkànlá.osu kejila odun 2020 ni ojo kẹrinlelogun osu kejila, arakunrin John nKengason, ti i se oludari ile-ise fun isakoso ati idena arun ni ile Afrika (director of the African centres for Disease Control and Prevention) so fun eekan iroyin ti ori ero ayelujara lati ilu Addis Ababa pe won tun ti se awari eya arun korona tuntun miran ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Bí èèkó Nkenga ti kede rẹ̀ ní èyí "ó jẹ́ ẹ̀yà tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ó ti orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì àti orílẹ̀-èdè gugubí Afrika wà.”Ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn korona tuntun 19,0 ni ó seyo ní oṣù kejìlá, èyí tí ó mú kí àpapọ̀ iye àwọn isele àrùn yi ti won ti fidi re mule lo soke si 86,576..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti ara won ti ya lo soke si 73,322, nigbati o wa seku 11,976 awon alaisan ti won n gba itoju lowolowo ni opin osu kejila yi.osu kinni odun 2021 orile-ede Naijiria de ipele ogorun oke(100,000) awon isele ti won ti fidi won mule ni ojo kewa osu kinni odun 2021..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ àrùn ti B.1.1.7 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kínní..
wikipedia
yo
Awon isele tuntun 44,666 ni o tun seyo ni osu kinni odun eyi ti o mu ki iye apapo awon isele ti won ti fidi re mule lo soke si 131,242..
wikipedia
yo
Awon alaisan ti ara won ti ya lo soke si 104, 989 ti o si wa seku awon alaisan 26,667 ti won n gba iwosan lowolowo ni opin osu January.<noinclude>àwọn isele tuntun 24,415 ni o seyo ni osu keji odun 2021 eyi ti o mu ki apapo iye awon isele ti won ti fidi e mule di 155,65..7..
wikipedia
yo
Iye awon alaisan ti ara won ti ya lo soke si 133,látinú, ti o si wa seku awon alaisan 19,982 ti won n gba itoju lowolowo ni opin osu keta odun 2021.Ìgbì eleekeji Akowe Ijoba apapo ati Alaga agbofinro fun ijoba lori arun COVID-19, Ogbeni BOSS Mustapha so ni ojo Thursday, ojo kewa, osu kejila odun 2020 pe ipele keji ajakale-arun korona ti bere leyin igba ti won ti se akiyesi wipe iye awon isele arun COVID-19 tun ti n lo soke si ni orile-ede Naijiria.Ki o to di wipe arun korona yi tun seyo ni eleekeji, igbagbọ opo eniyan ni wipe arun yi ti kase kuro nile ni orile-ede yi latipase bi awon isele arun yi se dinku gidigidi ti o fi je wipe awon ipinle miran ko tile se akosile isele kankan lori arun yi fun opolopo ose..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gbàgbọ́ pé púpọ̀ nínú àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n ti lùgbàdì àjàkálẹ̀-àrùn yí ni ara wọn ti ma ń yá nítorí ètò àjẹsára tí ó lágbára tí wọ́n ní..
wikipedia
yo
Àwọn míràn ní Ìgbàgbọ́ wípé èyí tí ó pọ̀jù lọ nínú àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí wọ́n ṣe Àkọsílẹ̀ wọ́n jẹ́ àrùn iba lásán..
wikipedia
yo
Awon miran tile n so pelu igbagbọ pe irinṣẹ́ ti won fi n se ayewo fun awon eniyan ko le fi iyatọ han laarin ẹran ati arun iba.ọpọlọpọ awon ti isele arun korona yi ti sele si, ti won si ti ri iwosan gba, je ko ye wa wipe opo ninu awon omo orile-ede Naijiria si gbagbo pe nse ni won n fi awon akosile isele arun ẹran korona yi tan awon eniyan je ni..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nba àwọn ènìyàn tí wọ́n gbàgbọ́ pé àrùn yí wa nítòótọ́ ń gbé ìgbé ayé àìbìkítà láì dáàbò bo ara wọn nítorí èrò wọn ni wípé àwọn aláṣẹ ṣe àfikún àkọsílẹ̀ iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkálẹ̀-àrùn yí nígbà tí ó kọ́kọ́ ṣẹ́yọ láti lè fi rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó gbà àti láti lè gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó sílẹ̀ fún àwọn ìpínlẹ̀ kí àwọn òṣìṣẹ́ kan lè fi di ọlọ́wọ́ látipasẹ̀ gbígbé àwọn iṣẹ́ àkànṣe sí ìta.Ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2020, Gómìnà Yahaya Bello ti ìpínlẹ̀ kogi sọ nínú fídíò kan láti ojú-ìwé Facebook rẹ̀ pé ìdá àádọ́rùn nínú ọgọrun (90%) ariwo tí ìjọba ń pá lórí àrùn COVID-19 ni ó jẹ́ wípé láti rí eréjẹ́ eré lórí ọ̀míràn àti ọ̀rọ̀ Ajé ni..
wikipedia
yo
O tun sọ wipe ida mewa ninu ogorun (10%) ti o ku je aisan otutu lasan ti awon omo orile-ede Naijiria ma n ni.laarin osu kesan si osu Kọkànlá odun 2020, lasiko ti ko fi be e si isenimole, opolopo awon isele ti won n se akosile won n dinku..
wikipedia
yo
Eto Oro-aje ni o tun di ṣiṣi pada lati le fi dẹkun ki ọrọ-aje mátun le mẹ́hẹ ni eleekeji..
wikipedia
yo
Àwọn ibi ìyara-ẹni-ṣọ́tọ̀ ti wọn wa ni àwọn ìpínlẹ̀ ni wọn tipa fún ìgbà díẹ̀..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kò kàn án nípa fún àwọn ènìyàn láti má a lọ Ìbomú ní àwọn ibi gbangba bí i àwọn ọjà, àwọn ilé-iṣẹ́, àwọn ibi ayẹyẹ, àwọn ilé oúnjẹ àti àwọn ilé ọtí.ì-sára-ẹni, èyí tí ó ṣe pàtàkì nígbà tí àrùn korona yí kọ́kọ́ ṣẹ́yọ ni àwọn ènìyàn tí kò sílẹ̀ látàrí bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ṣe ń kórajọ pọ̀ ní gbangba láì bọ̀wọ̀ fún ìlànà ètò ìlera.Ní ọjọ́ kẹwá oṣù kejìlá, Dókítà Osagie Eshaa, ẹni tí í ṣe mínísítà fún ètò ìlera sọ wípé ìpele kejì àrùn korona ń súnmọ́ nítorí iye àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ń pọ̀ sí látàrí bí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn yí ṣe ń pọ̀ sí ní àwọn agbègbè tí ó sì jẹ́ wípé díẹ̀ nínú wọn ní àwọn arìnrìn àjò tí ó ń wọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kó wọlé.Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wò ìpele kejì Àjàkálẹ̀-àrùn korona látàrí bí orílẹ̀-èdè yí tí ṣe ṣe àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun 1,145 àrùn COVID-19 ní Thursday, ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2020..
wikipedia
yo
Èyí jẹ́ iye ìsẹ̀lẹ̀ tí ó pọ̀jù nínú àwọn ìsẹ̀lẹ̀ àrùn yí tí ó ma ń ṣẹ́yọ lóòjọ́.Tábìlì ìṣiròàwọn Ìpínlẹ̀ kòkọnbinclude> àwọn ìjọba lórí àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19.Oṣù kẹta ní ìbẹ̀rẹ̀ Oṣù Kẹta, Alákòso fún ètò ìlera ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Minister of Health, Osagie esharẹ̀ ṣe ìkéde pé àwọn ènìyàn ọgọ́ta tí wọ́n ti ní ìfarakanra pẹ̀lú aláìsàn ará ilẹ̀ Itali ti dáwà ní ibìkan..
wikipedia
yo
Ogoji ninu àwọn eniyan yí wá láti ìpínlẹ̀ ogun nígbàtí ogún wà láti ìpínlẹ̀ Èkó.Ní ọjọ́ kini oṣù kẹta, àwọn ará orílẹ̀ èdè Chinese mẹrin ni wọ́n yà sọ́tọ̀ ní ìpínlẹ̀ Plateau..
wikipedia
yo
Àyẹ̀wò fìdí rẹ̀ múwa ni ojo keji pe won ko ni arun COVID-19.Ni ojo keta osu keta, gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu so wipe awon ajeji meji, ti won ko daruko won, lati orile ede Asian ko ni ajakale arun yi latari esi ayewo ti won se fun won.Ni ojo kefa osu keta, ijoba ipinle Anambra se ikede pe awon ara orile ede Chinese marun un ti won se ayewo fun ko ni arun..
wikipedia
yo
ilé iṣẹ́ tó un darí dídènà àrùn ní ilẹ̀ Nàìjíríà (The Nigeria Centre for Disease Control) sọ wípé àpapọ̀ iye àwọn tí àwọn tọ́kasí sí wípé wọ́n kọ́kọ́ ní ìfarakanra àti àwọn tí wọ́n ní ìfarakanra tẹ̀lé wọn tí wọ́n to 219 níye ní àwọn tí mo dájúdájú tí àwọn sì ti ń bójú tó wọn.Ní ọjọ́ Kẹ́sà oṣù kẹta, Ààrẹ Muhammadu Buhari fi Ìgbìmọ̀ tí yíò ma jábọ̀ fún Ààrẹ lórí ọ̀nà láti dẹ́kun àrùn yí ní Nàìjíríà lélẹ̀.Ní ọjọ́ kẹwa oṣù kẹta, ọkọ̀ òfurufú ti orílẹ̀ èdè TurKiṣi fagilé gbogbo ìrìn àjò wa sí ilẹ̀ Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn tí ó bẹ́ sílẹ̀.Ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, arábìnrin kan ní ìpínlẹ̀ Enugu ṣe ìfarahàn ààmì àìsàn Corona ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kejì ni Àyẹ̀wò fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé koni àrùn yí.Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 2020, ilẹ̀ Nàìjíríà sùn, àjọ̀dún aré ìdárayá tí ó jẹ́ ogún irú ẹ̀ (20th National Sports Festival) tí ó yẹ kó wáyé ní ìlú Benin, ìpínlẹ̀ Ẹdó, láti ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta sí ọjọ́ kíní oṣù kẹrin, síwájú di ìgbàmíràn.Ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta, àwọn alákóso àjọ tí ó ń risi àwọn ọ̀dọ̀ tó ń ṣiṣẹ́ sin ìlú National National Service Corps(NYSC) ṣe ìdádúró aláì sí ètò ìdárayá ìdárayá mọ́kànlélógún fún àwọn olùkópa owó kíní ti ọdún 2020..
wikipedia
yo
Eto idaraya ti o bẹrẹ ni ọjọ kewa Oṣu Kẹta ti o si ye ki o wa sópin ni ogbon ojo osu keta ni won da duro leyin ti won ti lo ojo mejo..
wikipedia
yo