cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ìjọba ìpínlẹ̀ Taraba kéde tìpa àwọn ẹnubodè wọn lẹ̀sẹ̀kẹsẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta tí wọ́n kọ́ sì jẹ́ kí lílọ àti bíbọ̀ wáyé ní ìpínlẹ̀ wọn.Ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì gbé òfin kónílé ó gbélé kalẹ̀, wọ́n ti àwọn ẹnubodè, wọ́n sì fi òfin de lílọ àti bíbọ̀ fún ọjọ́ mẹ́rìnlá yàtọ̀ sí àwọn ọkọ̀ tí ó ń gbé oúnjẹ, nkan èlò fún ìtọ́jú àwọn aláìsàn, epo Enper àti àwọn nkan míràn tí ó ṣe pàtàkì láti ọgbọ̀n ọjọ́, oṣù kẹta.. | wikipedia | yo |
Ìjọba pàṣẹ ki àwọn ará ìlú fìdí mọ́lé yàtọ̀ sí àwọn tí ó ń ṣe iṣẹ́ pàtàkì.. | wikipedia | yo |
Ìjọba tún pàṣẹ kí wọ́n ti gbogbo ilé iṣẹ́ okóòwò àti ilé ìjọsìn pa.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Anambra kede ki won ti Afara ti River Niger lesekese sugbon won ni ki won fi aaye gba awon oko ti won n ko ounje ati oogun.. | wikipedia | yo |
ìjjoba apapọ pase isemole fun ipinle Eko, Ipinle Ogun ati Abuja fun ose meji bẹrẹ lati aago mọkanla alẹ ogbon ojo osu keta, nigba ti won fi ofin de irin ajo lati ipinle kan si ekeji.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun ti gbogbo ile ise okoowo ati ọfiisi, yato si awon ile iwosan, ile ise ounje, ile epo Enbolu, ile ifowopamo, ile ise aabo aláàdani, awon ile ise ti o n risi eto ikansiara ati awon oniroyin ti won ko le se ise lati ile won.. | wikipedia | yo |
Ijoba apapo tun da gbogbo irin ajo awon ọkọ ofurufu ti ijoba ati ti aláàdani duro.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Osun kede titi Ẹnubodè Ipinle won pa lati ojo kokanlelogbon osu keta, won si fi ofin de lilo ati bíbò lati ipinle kan si ekeji yato si awon ti o n se ise pataki bi i awon osise aláàbò, awon olutọju alaisan ati awon ti o n ta ounje.Ní ogbon ojo osu keta, ijoba ipinle Adamawa pase titi awon Ẹnubodè Ipinle na pa bẹrẹ lati ojo kokanlelogbon osu keta, pelu ase pe ki o maṣe si lilo ati bíbọ̀ awon eniyan, awon ọkọ akero ati oko takisí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún pàṣẹ pé kí gbogbo ọjà di títìpa yàtọ̀ sí àwọn tí ó ń ta oúnjẹ àti oògùn.. | wikipedia | yo |
Fífi òfin de lílọ àti bíbọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn tí ó yẹ kí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọgbọ̀n ọjọ́, oṣù kẹta ni wọ́n sún síwájú di ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin lẹ́hìn tí ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti tọrọ gááfárà lọ́wọ́ ìjọba àpapọ̀ pé kí wọ́n fún àwọn láàyè láti pèsè oúnjẹ fún àwọn ará ìlú.Ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ìjọba ìpínlẹ̀ Bauchi kéde títí gbogbo ẹnubodè wọn pa fún ọjọ́ mẹ́rìnlá bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejì oṣù kẹrin, wọ́n tún pàṣẹ kónílé ó gbélé yàtọ̀ sí àwọn ènìyàn tí ó ń pèsè iṣẹ́ pàtàkì fún ará ìlú.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Kwara kede titi gbogbo awon ẹnubodè won pa fun lilo ati bíbọ awọn ọkọ lesekese yato si awon oko ti o n ko nkan ogbin, ohun elo fun itoju awon alaisan ati awon osise ti o n se ise pataki.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Delta se atunyẹwo Ẹnubodè wọn ti won ti tipa ati ofin ti won ti fi de lilo ati bíbọ̀, won si tun kede fifi aaye gba awon ti won n fi oko ko nkan pataki bi i ounje, omi, epo pésẹ̀ge, oogun ati wipe ki awon ile ifowopamo ma a sise fun igba die.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Bàtata na ṣe àtúnyẹ̀wò ẹnubodè wọn tí wọ́n ti tipa tẹ́lẹ̀ láti le fi ààyè gba àwọn ọkọ̀ tí ó ń kọ oúnjẹ, òògùn àti àwọn ènìyàn tí ó ń ṣe iṣẹ́ pàtàkì.. | wikipedia | yo |
Ni ọjọ́ yi kanna ni ìbákẹ́dùn waye pe pẹlu bi wọn ti ṣe ti gbogbo agbègbè pa ní ìpínlẹ̀ Èkó, ó ma jẹ́ ìṣòro fún ọ̀pọ̀ àwọn olùgbé ìlú láti pèsè oúnjẹ fún ara wọn àti fún àwọn ọmọ wọn.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ẹ̀dùn ọkàn fún wọn pé tí àwọn eniyan bá lọ sí oko wọn ní ìdàkejì ìlú, wọ́n lè ṣèèṣì kó àjàkálẹ̀ àrùn corona ran àwọn ìbátan wọn.Oṣù kẹrin ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹrin, ọdún 2020, ìjọba ìpínlẹ̀ Taraba fi òfin de gbogbo ìpéjọpọ̀ tí ó bá ti ju eniyan ogún lọ.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun paṣẹ ki won ti gbogbo oja pa lesekese yato si awon ile itaja oogun, ile ounjẹ ati ile epo pẹtiróòlù.. | wikipedia | yo |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó kéde títí ẹnu ibodè wọ́n pa bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Ní Oǹdó, ìjọba tún gbẹ́gidínà àwọn arìnrìn-àjò láti ìpínlẹ̀ mìíràn wá sí Òndó.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ kejì oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Bauchi ṣe ìdápadà òfin lílọ àti bíbọ̀ ní ìpínlẹ̀ nã.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Akwa Ibom kede pe ki o ma se si lilo ati ikun rara, ki gbogbo ara ilu fidimo ile won.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun ti gbogbo ile ise okoowo, awon oja, awon ibudo oko ati awon enitici pa sugbon awon ti won n ta ounje, oogun ati awon ti won n pese ise pataki fun awon ara ilu ni won gba laaye lati sise.Ni ojo karun un osu kerin, ijoba ipinle Niger mu ase ti won ti koko pa lori igbele rọrùn nipa pe ki lilo ati bíbo awon eniyan ma a waye lati aago mẹjọ owuro si aago meji osan lojoojumọ, subgon ko gbọdọ si lilo ati ikun lati aago meji osan si aago mewaa ni.Ni ojo kesan an osu kerin, ijoba ipinle Kwara fi ofin de lilo ati bíbo awon eniyan ni ipinle won fun ojo merinla lati ojo ojo kerin osu kerin.. | wikipedia | yo |
Ìjọba fi ààyè gba àwọn tí wọ́n ń ta oúnjẹ àti oògùn láti ṣe iṣẹ́ ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ rù, àti ọjọ́ Ẹtì láàrín aago mẹ́wàá òwúrọ̀ sí aago méjì ọ̀sán.Ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra fi òfin de lílọ àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́rìnlá, wọ́n sì pàṣẹ pé kí gbogbo olùgbé ìlú fìdímọ ilé Wọ́n fìyàtọ̀sí àwọn tí ó ń pèsè iṣẹ́ pàtàkì fún àwọn ará ìlú.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Niger fi ofin de lilo ati bíbọ̀ ni ipinlẹ wọn lati ojo ketala osu kerin yato si awon ti o n se ise pataki.Ni ojo ketala osu kerin ijoba apapo fi ose meji kun iye ojo ti won ti koko so wipe ko ni si lilo ati bíbọ̀ ni Ipinle Eko, Ipinle Ogun ati Abuja lati aago mokanla ale ojo ketala osu kerin.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Èkìtì nã fi ọjọ́ mẹ́rìnlá kún iye ọjọ́ tí kò fi ní sí lílọ àti bíbọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì.Ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà àti Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun fi ọjọ́ mẹ́rìnlá kún iye ọjọ́ tí kò fi ní sí lílò àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn ní ìpínlẹ̀ wọn.. | wikipedia | yo |
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano fi òfin de lílọ àti bíbọ̀ ní ìpínlẹ̀ wọn fún ọjọ́ méje bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kẹrin, nígbà tí wọ́n ní kí àwọn ará ìlú fìdímọ́ ilẹ̀, wọ́n sì ti àwọn ojà, àwọn ilé ìjọsìn àti gbogbo ibi ìpéjọpọ̀ àwọn ènìyàn pa.Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin, ó kéré tán, àwọn ènìyàn méjìdínlógún ní ilẹ̀ Nàìjíríà ní ìròyìn sọ wípé àwọn agbófinró ti pá lásìkò tí wọ́n ń gbìyànjú àti ṣe àfimúlẹ̀ àwọn ìgbésẹ̀ tí àwọn ìjọba ń gbé láti dáwọ́ ìtànkálẹ̀ àrùn un corona dúró.Ní ogúnjọ́ oṣù kẹrin, ilẹ̀ Nàìjíríà fi ọ̀sẹ̀ méjì kún iye ọjọ́ tí wọ́n ti kọ́kọ́ fi ti àwọn pápá ọkọ̀ òfurufú pa.. | wikipedia | yo |
Ijọba ipinlẹ Borno fi ofin de lilo ati bíbọ̀ ni ipinle na fun ojo merinla bẹrẹ lati ojo kejilelogun osu kerin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún fi òfin dé ìpéjọpọ̀ àwọn ènìyàn ṣùgbọ́n wọ́n gba àwọn tí ó ń pèsè iṣẹ́ pàtàkì fún ìrọ̀rùn àwọn ará ìlú.Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Taraba kéde títipa ìpínlẹ̀ wọ́n bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin, nígbà tí wọ́n fi òfin de lílọ àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn àti ọkọ yàtọ̀ sí àwọn òṣìṣẹ́ tí ó ń ṣe iṣẹ́ pàtàkì bí i àwọn olùtọ́jú aláìsàn, àwọn ilé ìtajà òògùn àwọn ilé epo Pper àti àwọn oníròyìn.Ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara fi ọ̀sẹ̀ méjì kún iye iye tí kò fi ní sí lílò àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn.Ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra gbé ẹsẹ̀ kúrò lórí òfin lílọ àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn.Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna fi ọgbọ̀n ọjọ́ kú iye ọjọ́ tí kò fi ní sí lílọ àti bíbọ̀ àwọn ènìyàn ní ìpínlẹ̀ wọn.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ìjọba àpapọ̀ kéde títí ìpínlẹ̀ Kano pa fún ọ̀sẹ̀ méjì lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun fi ose kan kun iye ojo ti won ti koko fi ti Ipinle Eko, Ipinle Ogun ati Abuja pa tele.. | wikipedia | yo |
Ìjọba àpapọ̀ tún ṣe òfin kónílé ó gbélé ìwàran gbogbo orílẹ̀-èdè bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹrin oṣù karùn ún láti aago mẹ́jọ àṣálẹ́ sí aago mẹ́fà òwúrọ̀ títí di ìgbà tí wọn kò ì ti lè sọ, nígbà tí wọ́n tún fi òfin dé àwọn ìrìn-àjò tí kò kan dandan láti ìpínlẹ̀ kan sí òmíràn.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún sọ wípé ó kan dandan fún àwọn ènìyàn tí wọ́n ń rin kãkà ní ìgboro láti lọ Ìbomú bẹnu (face masks).. | wikipedia | yo |
Ìjọba sì tún sún òfin tí wọ́n fi dè ìpéjọpọ̀ àwọn ayẹyẹ àti ti ẹ̀sìn síwájú.. | wikipedia | yo |
Ijoba Ipinle Anambra kede pe awon ti pada si awon oja mẹtalelọgọta ti o se pataki ni ipinle na.Ni ojo kejidinlogbon osu kerin, ijoba ipinle Delta kede pe awon ti mu ki ofin ti awon fi de lilo ati bíbo awon eniyan rorun lati ogbon ojo osu kerin.osu karun un ni ojo kejo osu karun un, ijoba ipinle Abia kede imurọrùn si ofin isemole lati ọjọ́ọ́ Kọkànlá osu karun un.Ni ojo kejidinlogun osu karun un, ijoba apapo fi ose meji kun igba ti ko fi ni si lilo ati bíbọ̀ ni Ipinle Kano, nigba ti ijoba tun fi ose meji kun ofin kónílé o gbele ti o n waye lowolowo ni orile-ede Naijiria.Awon itọsinaìjìibeNàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ikú ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó wà ní iwájú ọrùn gbogbo ẹranko elégungun.Iṣẹ́ rẹ̀gògòńgò ni ó ń ṣàkóso bí ohun jíjẹ àti mímu kò ṣe ní gba odi nípa ṣíṣètò ìyàtọ̀ láàrín ìròọ́n ọ̀fun, ohun àti taàná tí ó gbé èémí jáde nígbà tí a bá ń jẹun lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
gògóńgò tí a n sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí náà ni ó tún gbé ọ̀pá ẹ̀jẹ̀ (Blood Vekab) Orisirisi.. | wikipedia | yo |
gògóńgò ẹranko elégungun ni Orisirisi eégún meji ti a mọ si (Egungun (Egungunyoid) ati (Clavilélé).Ewe, gògóńgò tun n ṣiṣẹ pẹlu ẹnu, Eti,imú ati pupo ninu awọn ẹya ara gbogbo.Àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ẹranko elégungun ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ lára ẹbí (subgbogbobẹ̀rẹ̀) ẹranko elégungun ma ń saba ní ṣùọdúntes (Egungun ẹ̀yìn).. | wikipedia | yo |
Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí tẹ́júpìpamọ́— tí wọn tó ẹgbẹ̀rún le láàdọ́rin àti ọgọrun un ó dín meje (69,963, níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn.. | wikipedia | yo |
Ti orúkọ àbísọ rẹ̀ gangan ń jẹ́ Azeez Faṣọ, tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kesàn-an Oṣù karùn-ún Ọdún 1994 (9th May 1994) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin àti Onpìlẹ̀-orin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni Ààrẹ ẹgbẹ́ olólùfẹ́ Àgàbàgebè rẹ̀ tí wọ́n ń pè ní "Marlians".Igba Ewe ati Àko kòpò bí naira Marley ní ìlú Agege ní Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó wà lọ́mọdún mọ́kànlá ní ó dèrò ìlú ìjídì, ní Leekam, lápá gúùsù London, lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Porlock Hall kí ó tó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Walworth School, níbi tí ó ti gbàwé ẹ̀rí General Certificate of Secondary Education.. | wikipedia | yo |
Naira Marley kawe gbawẹ ẹ̀ri ti o ga julọ ninu imo okoowo ni ile-ẹkọ Harris Academy ni ilu wẹbkam Peckham.. | wikipedia | yo |
Ó tún kàwé gbáwẹ ẹ̀rí nínú ìmọ̀ òfin okoowo ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Crossways College tí wọ́n ń pè ní Christ the King sixth Form College .Àtòjọ àwọn orin rẹ̀orin Alajokothitta Dance (2015) of Lamba (2019)orin aládàáko"sa Goal" (2017)" (2018" (2018 í a Yahoo Boy" (2019)"yi (Marli)" (2019)" (2019” (2019bAB) (2019)"" (2019)" (2019)" (2019) (2019) Àwọn Amin-Eye tí ó gbà àti àwọn tí wọ́n yàn án fúnàwọn Ìtọ́kasíàwọn akọrin ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
(Ọjọ́ìbí April 6, 1937) jẹ́ òṣèré, òṣèré gbohùngbohùn àti Oníṣẹ́ònà Ara Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasí ara fíAna AraAmégbọ̀n Ọmọ Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Shettima Mustafa OFR (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kọkànlá ọdún 1939 - 2022) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti olósèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn láàrin ọdún 1990 sí ọdún 1992.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2007 wọ́n yan Shettima gẹ́gẹ́ bi Mínísítà fún abọ́ sínú ẹ̀tọ́ ìṣàkóso ti Umaru Yar'Adua.. | wikipedia | yo |
Shettima fi offici sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Mínísítà ní oṣù kẹta ọdún 2010 nígbàtí adelé Ààrẹ Goodluck Jonathan tu ìgbìmọ̀ ìṣàkóso rẹ̀ ká.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ Shettima Mustafa ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kọkànlá ọdún 1939 ní Nguru, agbègbè tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Yobe bálélé.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Borno Middle ní Maiduguri laarin ọdún 1946 si ọdún 1952.. | wikipedia | yo |
Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi Medical Field Assistant ní Kano láàrin ọdún 1955 sí ọdún 1956.. | wikipedia | yo |
O tun sise ni Borno Native Administration laarin odun 1954 si odun 1964 ki o to di wipe o lo sise pelu ile ise radio Television ti Kaduna laarin odun 1965 si odun 1967.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí Shettima pé ọmọ ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n ní ọdún 1967, wọ́n gbà á gẹ́gẹ́ bí akọ ẹ̀kọ́ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Ahmadu Bello .. | wikipedia | yo |
O kọ ẹkọ gboye ni ọdun 1972 ti o si bẹrẹ iṣẹ gẹgẹ bi oluwadi ijinle pẹlu ile-ẹkọ giga fun iwadi ijinle lori awon nkan ogbin.. | wikipedia | yo |
Láti ọdún 1973 sí ọdún 1974, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga ìYunifasiti ti Cambridge níbití ó ti gba ìwé ẹ̀rí onípele gíga ti ìlọ́lọ́we (Post) nínú Applied Bioba Bibi.. | wikipedia | yo |
O te siwaju ninu ẹkọ rẹ lati gba iwe ẹri imọ ìjìnlẹ̀ (PhD) nigbati o lọ si ile-ẹkọ giga Yunifasiti ti purdue, Indiana ni Ilu Amẹrika ni ọdun 1978.. | wikipedia | yo |
Shettima tún parí ẹ̀kọ́ kan lórí Agricultural Project monitoring and Evaluation ní Yunifásítì ti East Anglia ní ọdún 1990.Iṣẹ́ ìlú Shettima Mustafa ní wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bi kọmíṣọ́nà sínú ìjọba ní Ìpínlẹ̀ Borno lábẹ́ Gómìnà Mohammed Goni.. | wikipedia | yo |
Shettima ń gòkè ní ṣísẹ̀ntẹ̀lé nínú ipò òṣèlú títí ó fi di wípé wọn yàn án gẹ́gẹ́ bí olùkéde fún igbákejì Ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Nigeria People's Party nínú ìdìbò ti ọdún 1983.. | wikipedia | yo |
Síbẹ̀síbẹ̀, aláṣẹ Shehu Shagari ti ẹgbẹ́ Òṣèlú National Party of Nigeria ló bori ninú idibò yi.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn tí àwọn ológun fi ipá gbà ìjọba ní Oṣù kejìlá ọdún 1983 nígbàtí ọ̀gá Muhammadu Buhari gun orí àléfà, wọ́n fi Shettima sínú ẹ̀wọ̀n títí di ọdún 1985.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí ó jáde nínú ẹ̀wọ̀n, ó padà lọ sẹ́nu iṣẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Maiduguri.. | wikipedia | yo |
Lẹhinna ni o di olori Smoke ni Ile iṣẹ Ijọba apapọ ti o nri si eto ogbin (Federal Ministry of Agriculture) ni Ilu Jos.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹjọ Ọdún 1990, wọ́n yan Shettima Mustafa gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn àti ohun àlùlùlù (Minister of Agriculture and Natural Resources).. | wikipedia | yo |
Ori ipo yi ni o wa titi di igbati wọn fi tu Igbimọ Minisita ka ni ọdun 1992.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ìwọ̀nyí, ó di olùdámọ̀ràn fún orísirísi àwọn àjọ ilé-iṣẹ́ ní agbègbè àti ni ìlú òkèèrè.. | wikipedia | yo |
Ó sì tún di akápò ti orílẹ̀ èdè fún ẹgbẹ́ àlábúradà (people's Democratic Party).. | wikipedia | yo |
Awon bi i Fellow of the Genetic Society of Nigeria, American Society of AGRonomy ati omo egbe awujo awon onimo nipa ogbin ni ile Naijiria (Agricultural Society of Nigeria).. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2002, wọ́n yan Shettima Mustafa sínú ìgbìmọ̀ olùdarí ilé ìfowópamọ́ ti Savannah, bótilẹ̀jẹ́pé kì í ṣe ọ̀kan lára àwọn alájọpín ìdókòwò.Mínísítà Yar'Adua Alakoso orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Umaru Yar'Adua yan Shettima gẹ́gẹ́ bi Mínísítà fún ẹ̀tọ́ àbò.. | wikipedia | yo |
Ni ọjọ kerinla oṣu keje ọdun 2008, o paro aye pẹlu [ [Godwin Abbe] ] lati di Minisita fun Interior.Awọn itọkasi awọn oloselu ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àyàfi àwọn tí a mọ̀ sí ìlàrí ọba, tí wọ́n máa ń fi díẹ̀ lé nínú orí wọn láti fi hàn pé ìlàrí níwọ̀n... | wikipedia | yo |
Ayọrinde Fasanmi (tí a bí ní ọdún 1925-2020) jẹ́ onímọ̀ nípa òògùn àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé a bí ayòrìndé Fasanmi ní ọdún 1925 ní iye Èkìtì, agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ní Gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákokobẹ̀rẹ̀ ti Saint Paul tí ó wà ní Èbúté Mẹ́ta àti ilé-ìwé ìjọba tí ó wà ní Ìbàdàn kí ó tó wa tẹ̀síwájú lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa egbògi tí ó wà ní Yaba níbití ó ti gba ìwé ẹ̀rí diploma lórí ìmọ̀ nípa egbògi.. | wikipedia | yo |
Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ nípa oògùn ní Oshogbo fún ìgbà dì ẹ́ kí ó tó di wípé ó darapọ̀ mọ́ òṣèlú ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Iṣẹ́ òṣèlú Fasanmi darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú oníṣọ̀kan ti ilẹ̀ Nàìjíríà (Unity party of Nigeria) ní ọdún 1978.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adíje nínú ìdìbò abẹ́lé fún ipò gómìnà ní ìpínlẹ̀ Oǹdó sùgbọ́n Ó pàdánù ìdìbò abẹ́lé yí sí ọwọ́ Michael Adékúnlé Ajasin, ẹni tí ó jẹ́ gómìnà tẹ́lẹ̀ fún ìpínlẹ̀ Oǹdó.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1983, wọ́n dìbò yan Fasanmi gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú kékeré ti gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (Federal House of Representative) láti lọ ṣe aṣojú fún àríwá ìpínlẹ̀ Òndó.. | wikipedia | yo |
Lehinna, ó ṣiṣẹ́ sin gẹ́gẹ́ bi ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ olùdarí fún ila oorun àtijọ́ Nàìjíríà lórí àwọn ilẹ̀ alákọ̀ọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò òṣèlú ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin ní Nàìjíríà, Fasanmi tún ṣiṣẹ́ sìn gẹ́gẹ́ bí igbákejì alága fún ẹgbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy ti agbègbè gúúsù ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìgbésí ayé rẹ Fasanmi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú olóògbé ìyáàfin àjọkẹ́ ẹnití ó di olóògbé ní ọmọ ọdún méjìlélọ́gọ́rin ní oṣù kẹwa ọdún 2014.Àwọn ìtọ́kasí àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ambrose Campbell ti Orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Oladipupo Adekoya Campbell tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọ́kàndínlógún oṣù Kẹjọ ọdún 1919, ó sìn kú lọ́jọ́ méjìlélógún oṣù kẹfà ọdún 2006 (19 August 1919 – 22 June 2006) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin àti adarí orin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni wọ́n gbà pé ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ olórin àwọn adúláwọ̀ àkọ́kọ́ tí wọ́n ń pè ní The West African Rhythm Brothers lórílẹ̀-èdè Bìrìtì ní nǹkan bí ọdún 1940, bẹ́ẹ̀ náà gbajúgbajà olórin Fela Anikulapo Kuti náà gbà pé òun ni bàbá àwọn olórin ìgbàlódé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O sise pelu opo awon olorin jazz lórílẹ̀-ede Geesi ni nnkan bi odun 1950, paapaa ju lo, Leon Russell ti o ba sere kiri, ti o sin tun ba se awo-orin po lórílẹ̀-ede Amerika, nibi ti o gbe fun ogbon odun gbáko.Ìtọ́kasí are Ambrose Campbell at Discogs.com itọkasiàwọn olorin ara Naijiriàwọn omo YORÙ ara Naijiria meta lókèrè.. | wikipedia | yo |
Àṣà ilà kíkọ ni ilẹ̀ Yorùbáila kíkọ jẹ́ n kan pàtàki ti àwọn ọmọ Yorùbá fi n dara wọn mọ ni ayé Ojo.. | wikipedia | yo |
Òwe Yorùbá kan sọ pé títa ríro ni a ń ko ilá, ṣùgbọ́n bí ó bá jìnà tán, a di oge.Ní ìgbà àtijọ́, àṣà ilà kíkọ jẹ́ ohun àmúyangan àti ara oge ṣíṣe fún tọkùnrin-tobìnrin ní ilẹ̀ Yorùbá.Bí a bá wo ojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, a ó rí oríṣiríṣi ìlà lójú wọn.. | wikipedia | yo |
Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn ni kò mọ ìdí rẹ̀ tí a fii kọ ilá.Àwọn kan gbà wí pé ẹrú ni wọ́n kọ́kọ́ kọ nílà láyé ọjọ́un fún ìjìyà ẹ̀sẹ̀ ẹrú náà.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n nígbà tó jìnà tán ló di wí pé, Ìlà ojú rẹ ń wu gbogbo ènìyàn.Kíni ìdí rẹ̀ tí a fi kọ ilà?Nígbà láéláé, ogun àti ọ̀tẹ̀ pọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Lákokò yìí ni ọmọ ń sọnù láìrò-tẹ́lẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn alágbára ń kọ́ àwọn ọmọ ẹni tí kò ní agbára bí tí wọ́n ta.. | wikipedia | yo |
Bí n wọ́n ti ń kọ́ ọmọ wọn bẹ́ẹ̀ ni n wọ́n ń kọ aya wọn pàápàá.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ni ọ̀pọ̀ géńdé ní í sọnù, tí à ń fi wọ́n ṣe awaàti láwùjọ.Bí a ti ń kọ́ wọn là ń tàwọn lẹ́rú fún àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.. | wikipedia | yo |
Bí àwọn tí a tà lẹ́rú wọ̀nyí, yálà láti ìdílé kan náà tàbí ìlú kan náà bá pàdé, wọn kò ní mọ ara wọn rárá.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n àwọn àgbàlagbà ronú pé ó yẹ kí kíní kan bí àmì wà, èyí tí ń wọn yóò fi máa mọ̀ ara wọn.Tí wọ́n ó sì lè sọ lẹ́sẹ̀kan náà nípa ìlú tí ènìyàn kan ti wà ní kété tí àbá ríi.. | wikipedia | yo |
Ọgbọ́n ilà kíkọ yí kìí ṣe ti gbogbo orílẹ̀-èdè yìí ni láti ìbẹ̀rẹ̀ bíkòṣe ohun tí àwọn eniyan orílẹ̀-èdè yìí jogún láti ìwọ̀-ọ̀run níbi tí àṣà náà ti kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀.Ìdí keji tí a fi kọ ilà ìdí ni pé bóyá àwọn eniyan ìwọ̀-ọ̀run níbi tí àṣà yìí ti bẹ̀rẹ̀ rò pé yóo bukun ẹwà ara wọn nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀.Bí a bá wọ́ ju ẹlòmíràn ninu àwọn ọkunrin tabi àwọn obinrin tí ó kọ ilà, a ó ri pé ilà náà dára pupọ lójú ọpọlọpọ wọn.. | wikipedia | yo |
Dájúdájú, àṣà láti bù sí ẹwà ara ni irú àwọn bẹ́ẹ̀ ka ilà kíkọ sí.. | wikipedia | yo |
Bí a bá wo fínnífínní, a ó ri pé ilá yi yàtọ̀ sí ara wọn lati agbègbè si agbègbè tabi ìlú si ilú níbòmíràn.Àwọn Ọ̀yọ́ níí kó oriṣiriṣi àbàjà, pẹ̀lẹ́ ati ture.. | wikipedia | yo |
Nwọ́n tún n kọ́ àbàjà mẹ́tà-mẹ́ta, tàbí Gọ̀í, kẹ́kẹ́ àti Gọ̀g papọ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn Èkìtì a bu mẹ́ta-mẹ́ta ti ó gbòòrò, tàbi ẹyọ kan ṣoṣo ti ó gbòòrò, tàbi mẹ́ta ọ̀rọ̀ lórí mẹ́ta ìbú ti ó gbòòrò.. | wikipedia | yo |
Àwọn Ẹ̀gbá ní ń kọ mẹ́ta-mẹ́ta tí kò gún tí kò sì gbòòrò.. | wikipedia | yo |
Àwọn Ìjẹ̀bú a máa kọ́ mẹ́ta-mẹ́ta tàbí mẹ́ta lókè, mẹ́ta ni ìsàlẹ̀ rẹ̀.Àwọn òwú náà ḿbù àbàjà, nwọ́n sì ḿbù kẹ̀kẹ́ pẹ̀lú.. | wikipedia | yo |
Púpọ̀ nínú àwọn ìfẹ́ kìí kọlà, ṣùgbọ́n àwọn míràn nkó mẹ́ta-mẹ́ta nígbà míràn.. | wikipedia | yo |
Àwọn Iyàgbà ńkọ mẹ́ta-mẹ́ta tí ó fẹ́ ẹ papọ̀ l'ẹ̀bá ẹnu wọn.Ogunlọ́gọ̀ ilé la ti pa àṣá yí rẹ̀, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé wa tí kò fẹ́ fi àṣà yìí sílẹ̀ rárá.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn àpẹrẹ irú àwọn ilá tí àwọn Yorùbá ma ń kọ nìwọ̀nyí láti fi dáwàlójú pé àwọn ìlá wọ̀nyí yàtọ̀ sí ara wọn láti ìlú àti ilẹ̀ sí ara wọn.sòfò ní àwọn ìla mẹ́ta tí a fa Síbẹ̀síbẹ̀ lórí ara wọn tàbí mẹ́fà tí a tó ní mẹ́ta-mẹ́ta àlásùn bákan náà.com Ménìyàtọ̀ tó wà láàrín eleyĩ àti èyí tó eà lókè yí ni pé.. | wikipedia | yo |
A bu ilá tòkè ní mẹ́ta-mẹ́ta, ṣùgbọ́n a bu eleyĩ ní mẹ́rìn-mẹ́rin.com alágbeleiru àbàjà eleyĩ ni a ma ń bú sí ojú ènìyàn tí a sì tún gbé mẹ́ta ọ̀rọ̀ míràn lé lórí.Pẹ̀lẹ́ mẹ́ta tí a fa ṣeréke tí ó dúró lóòró.. | wikipedia | yo |
Ṣíṣọ́ ní kẹ̀kẹ́ Olówu, bíbú ni kẹ̀kẹ́ Ọ̀yọ́.Pẹ̀lẹ́ Ifẹ̀ìlà mẹ́ta ọ̀rọ̀ìlà Òǹdóẹyọkan ṣoṣo tí ó gùn tí ó sì jinlẹ̀ nípele Ìjẹ̀búìlà mẹ́ta tí ó gùn díẹ̀ níàbàjà Ẹ̀gbámẹ́ta òró àti mẹ́ta ìbú, tí a kọ lórí ara wọn.Pẹ̀lẹ́ Ìjẹ̀ṣàmẹ́ta lóòrótítí Ìjẹ̀ṣàmẹ́rin ni ìbú.Pẹ̀lẹ́ àti àbàjà Èkìtìàwọn wọ̀nyí yàtọ̀ sí pẹ̀lẹ́ àti àbàjà tí a ti ṣàlàyé sókè nítorí pé nwọ́n gbòòrò púpọ̀ ju ti ìṣãjú lọ... | wikipedia | yo |