cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó tún rọ àwọn ilé-ìwé aládàáni àti ìjọba kí wọ́n dáwọ́ iṣẹ́ dúró..
wikipedia
yo
Kódà gbogbo ènìyàn ni gómìnà ìpínlẹ̀ náà rò láti dúró sílé..
wikipedia
yo
èyí ó sì yọ ilé-ìjọsìn ti Mùsùlùmí àti kite sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Àṣẹ sì wà pé kò gbọdọ̀ sí ìpéjọ pọ̀ tó ju ogún èèyàn lọ..
wikipedia
yo
yálà ní ilé-ìjọsìn, ayẹyẹ, ilé-iṣẹ́ àdáni tàbí ìpéjọ pọ̀ mìíràn lóríṣiríṣi..
wikipedia
yo
Àṣẹ sì wà pé ẹnikẹ́ni ti ọwọ́ bá tẹ̀, a fojú ba ìjìyà tó tọ́..
wikipedia
yo
Ìjọba náà fi lélẹ̀ pé kò gbọdọ̀ sí ìjáde tàbí ìwọlé pẹ̀lú ọkọ̀ òfúrufú ní ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Awon oja kaakiri ipinle naa ni o si ni ojo ti won n si fun tita ati rira..
wikipedia
yo
Àmọ́ àwọn òwà tó ń ta nǹkan ìré ní ààyé wà fún láti sí ṣọ́ọ̀bù wọn.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Òkèzie Victor IkpeAzu (Ọjọ́ìbí 18 Oṣù Kẹ̀wá 1964) ní Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí Orí àga ní May 29, 2015..
wikipedia
yo
Wọ́n tún dìbò sí ipò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá nínú ìdìbò tó wáyé ní March 9th, 2019.Ìtọ́kasí Gómìnà Gómìnà Ábíá Áánù..
wikipedia
yo
Ahmadu Umaru Fintiri (Ọjọ́ìbí October 27, 1967) ní Gómìnà ìpínlẹ̀ adáwà lọ́wọ́lọ́wọ́ ó fi tẹ̀lé jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Adamawa, níbití wọ́n tí yàn gẹ́gẹ́ bí olórí ilé aṣòfin..
wikipedia
yo
O di aropo Gomina Ipinle adáwa fun igba diẹ leyin igba ti Gomina Murtala nyako je yíyọkuro lori ipo na ni July 2014, ko to gbẹ́pọ̀ na fun Biku James NGilari leyin to lo osu meta lori Ibejijiji gomina ipinlewa Adamawa..
wikipedia
yo
Mayen ATÍ (tí a bí ní ọdún 1954) tí n ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ òṣèré tí ó wá padà di ọgbọ̀nkari onídọ́gba onímọ ẹ̀rọ.Ìgbésí ayé rẹ̀ a bí Adẹ́bita ní ọdún 1954 sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Iṣẹ to ni se pẹlu akooodo owo ni o fẹ kọkọ se amo o pada nífẹ̀ẹ si ise imo ẹrọ.O fẹ Dele Adetiba, won si bi omo meta, Kemi Adeti je okan lara awon omo won ti won bi si Ipinle Eko ni odun 1980.Iṣẹ rẹ ti ti fìgbà kan je osere ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ lórí The Bar Beach Show, ó sì ṣe ìyàwó Lakunle Òjó nínú eré village Headmaster..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu fíìmù kọngi Harvest tí ó jáde ní ọdún 1980.A yàn-án gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Association of Buijù PaFC of Nigeria, ó sì jẹ́ ìgbà kejì Ààrẹ ti Nigerian Society of Pavarro nígbà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akoko ti won fi se okan lara awon executive Committee ni Nigerian Society of Pavmueller..
wikipedia
yo
kíkọ́ African Union Southern Africa Regional Office tí ó wà ní Màláwì àti SummerHill Baptist Church ní Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ àwọn iṣẹ́ tí ó ti ṣe..
wikipedia
yo
O tun sise lori pro BONo ti won ko sise.eto eko re ile eko giga ni oke okun ni o lo..
wikipedia
yo
Níbi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ láti rán ara ẹ̀ lọ ilé-ìwé nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ ò rówó ránṣẹ́ sí nítorí àwọn ìdojúkọ kan..
wikipedia
yo
Ó wà ní New York University fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó gba ìsọdá sí Columbia University níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa bàìbàì Engineering..
wikipedia
yo
Civil Engineering ni ó padà ṣe nígbà tí wọ́n sọ fún pé Civil Engineering niyì ní ilẹ̀ Áfíríkà.Nigba tí ó yí ohun tí ó ń kọ́ ní Ifásitì náà sí Civil Engineering, ó já sí pé Adétí nìkan ní ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti aláwọ̀ dúdú tí ó ń kọ́ ẹ̀kọ́ náà..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀ síwájú láti gboyè master's degree ní Cornell University.Ní ọdún 2017, ó fojú hàn lórí ètò kan tí ọmọ rẹ̀ kemi gbé kalẹ̀ tí ń jẹ́ "King Women"
wikipedia
yo
O dara po mo awon King Women miiran bi i Chigul, Taiwo Aja-Ilytt, TY Bello ati Tara Dutòyeàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kemi Adetiba je omo orile-ede Naijiria ti o si je oludari fidio orin lóríṣiríṣi, asefiimu agbelewo ati oludari eto lori yasọnu ti awon ise re ti han lori Channel O, MTV Base , Soundcity TV, Bet ati Netflix .igbesi aye re ojo kejo osu kìíní odun 1980 ni a bi Kemi ni Ipinle Eko, iya re ni Mayen Ti ti o je onimo ero ati osere..
wikipedia
yo
Kemi Adetiba bere igbesi aye re sinu eto ori afefe nigba ti won fi se ipolowo ose omo..
wikipedia
yo
Èyí sì hàn pé ipa ẹsẹ̀ baba rẹ̀ délẹ̀ Adétibá lọ ń tó.Iṣẹ́ rẹ̀ Kemi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi agbetọ sórí rédíò pẹ̀lú Rhythm 93.7 FM, níbi tí ó ti ń darí ètò méjì kan tí ń jẹ́ “soul'd out” àti “Sunday at the Seside..
wikipedia
yo
KẸ́MI bẹ̀rẹ̀ sí ní fi àtúnkọ orin sí orí ẹ̀rọ Ayárabíàṣá bíi Smẹ́tàmẹ́tà àti SoundCloud láìfi orúkọ ara rẹ̀ síbẹ̀ àmọ́ ó ń lo orúkọ kan ti ń jẹ́ ‘Hu'.MI'.MI Aroko yí kúrò láti agbeto sórí rédíò sí agbeto sórí tàgbà..
wikipedia
yo
Ó ń gbé àwọn ètò bíi Studio 53, Temptation Nigeria pèlú ikpọnlórúkọ OisakiOduwa lórí MNET..
wikipedia
yo
O tun dari eto Maltíná dance all fun sáà mẹta.leyin odun meta pelu aseyori ninu ise re, Kemi foruko sile pelu New York Film Academy lati ko nipa awon ohun àmúyẹ fun awon to n dari fiimu..
wikipedia
yo
LÓNÌÍ, Kemi si ti di ogbontarigi oludari fiimu agbelewo ni orile-ede Naijiria ati Afirika..
wikipedia
yo
Fíìmù Isẹ́sẹ́ díẹ̀ tí Kemi Adetibá ṣe tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ Across a BlooDied Ocean ní àjọ Pan African Film Festival and National Black Arts Festival se Lameeto e.Ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kesan-an Ọdún 2016, Kemi Adeti kópa nínu fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ "Wedding Party".Ní ọdún 2017, ó jẹ́ olùdarí ẹ̀tọ́ kan lori Teli tí n jẹ́ "King Women" níbi tí ó ti gbé ìyá rẹ̀ Mayen Adeti sori afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Awon obinrin miiran ti o pe wa sori eto "King Women" naa ni Chigul, Taiwo Aja-Ilycett, TY Bello and Tara Durototóyè.ààtò awon ami eye rẹ̀ die lára àwọn àmì ẹ̀yẹ tí iṣẹ́ rẹ̀ ti bí ní fidio obìnrin tí ó dára jù lọ fún orin "Ekunst" láti ọwọ́ TY Bello ni Soundcity TV Music Video Awards, fidio obìnrin tí ó dára jù lọ fún orin "Today na today" láti ọwọ́ omawunmi ní 2010 Nigeria Entertainment Awards..
wikipedia
yo
Àwọn àṣeṣe ṣe iṣẹ́ rẹ̀ ní “pilẹ̀” ti wájẹ́ kò pẹ̀lú tiwa Savage, “Ani-ṣe” ti Olamide kọ ati bẹẹ bẹẹ lọ..
wikipedia
yo
a yan kémi gẹ́gẹ́ bíi olùdaríbìnrin tí ń gbé fídíò orin jáde tí ó dára jù lọ níThe Headies 2014 ní ọdún 2014..
wikipedia
yo
Udom Gabriel Emmanuel (Ọjọ́ìbí 11 July 1966) ní Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní Nàìjíríà, ó wà lórí àga lati 29 May 2015 lẹ́yìn Igbatòwe lẹ́yìn ìdìbò April 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party..
wikipedia
yo
Wọ́n tún túndìbò sípò Gómìnà ní ọjọ́ 29K Oṣù Karun ọdún 2019.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Priscilla Ekwere ẹlẹ́jẹ̀ jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ olùdarí iṣẹ́ tó ní ṣe pẹ̀lú owó tí à ń ná ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Central Bank of Nigeria (CBN)..
wikipedia
yo
Òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ìbuwọ́lù rẹ̀ hàn lórí owó tí à ń ná ní orílẹ̀-èdè náà.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ẹlẹ́jẹ̀ jẹ́ ọmọ ìlú àfitan ní ìpínlẹ̀ ẹbọnyí..
wikipedia
yo
Ó gba degree nínú psychology ní University of Jos, ní ìpínlẹ̀ Plateau..
wikipedia
yo
Humphrey Fellowship in Banking and Management ní Boston University, Massachusetts, USA..
wikipedia
yo
Bákan náà, ó jẹ́ cerTífí information system auditortor (cisa).ise re a yan ẹlẹ́jẹ̀ bíi subStantive director of Curd operations of the Nigerian apex bank, CBN, ní oṣù kẹjọ ọdún 2018..
wikipedia
yo
Síwájú ìgbà tí a yàn-án fún ipò yìí, ó jẹ́ adelé ipò náà..
wikipedia
yo
Owó kìíní àwọn owó tí ó ní ìbuwọ́lù rẹ nínú ni ẹgbẹ̀rún kan náírà tí ó yíká ní ọdún 2019...
wikipedia
yo
Yíyàn tí a yàn-án mú oríyìn wá látòde Àjọ lóríṣiríṣi tó ní ṣe pẹ̀lú obìnrin, pàápàá jù lọ The National Council of Women Societies (NCWws), ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ayọrinde Bamgbose (Ọjọ́ìbí Ọjọ́ 27 Oṣù Kíní, Ọdún 1932) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ẹ̀dá èdè, tí ó sì tún jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó gba Ọ̀yọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Ẹ̀dá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ ribi ribi nínú Ẹ̀kọ́ Ìmọ̀ Ẹ̀dá Èdè, tí ó sì ti di ìlú mọ̀ọ́ká àti gbajú-gbajà láàrín àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lágbo ìmọ̀ ẹ̀dá èdè.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Idìtẹ̀jọba ni Nàìjíríà ọdún 1966 bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún osù kíní, ọdún 1966, nígbà tí àwọn wón ti inú ń bíi Chukwuma Kaduna Nàmúyẹ*. àti Emmanuel Ifeaj tí wón pa ènìyàn mejilelogun..
wikipedia
yo
nínú èyí tí wọ́n pa Mínísítà àgbà fún ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, àwọn olóṣèlú Jankande Jankande, àwọn ọ̀gá sójà àti àwọn ìyàwó wọn..
wikipedia
yo
Àwọn adìtẹ̀gbàjọba kọ lu àwọn Ìpínlẹ̀ bíi Kaduna, Ìbàdàn, àti Èkó, nígbà tí wọ́n di ojú-ọ̀nà Niger àti ọ̀dọ́ Benue odidi ọjọ́ méjì gbáko ṣáájú kí wọ́n tó rí wọn mú..
wikipedia
yo
Ọ̀gágun àwọn ọmọ ohun ilé nígbà náà, Ọ̀gágun Johnson Aguiyi-Ironsi ni lati tẹ́wọ́ gba ìṣàkóso Ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà, ti ìṣàkóso àwọn olóṣèlú sì gbélé..
wikipedia
yo
Ggoroye Ironsi gori oye ni o jẹ iṣẹ ọwọ ati atilẹyin awọn adìtẹ̀gbàjọba gbogbo wọn si jẹ ẹya igbo..
wikipedia
yo
Àwọn sójà Hausa náà dìtẹ̀ gbàjọba padà tí èyí náà sì já sí ikú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn sójà àwọn igbó, tí èyí sì mú kí ogun abẹ́lé ilẹ̀ Nàìjíríà bẹ́ sílẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sínáìjììjìmeje Ìdìtẹ̀gbàjọba ológun ní Nàìjíríàogun abẹ́lé Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Regina Lee Hall (ọjọ́ ìbí December 12, 1970) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà sinimá àgbéléwò àti agbọ̀n ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amélwọ̀nwọ́n òṣèré tẹlifíṣàn ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Tísha Michelle Campbell (ojoibi October 13, 1968) jẹ́ òṣèré, akọrin àti oníjó ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní Oklahoma City, Oklahoma, ó sì dàgbà ní New Jersey, ó bẹ̀rẹ̀ eré fíú rẹ̀ ní 1986 nínu fíú aláwàdà Little shop of Horrors, ó sì kópa lẹ́yìn igbana nínu eré dírámà Ilé-R tẹlifíṣàn NBC tó ń jẹ́ Dailyde tó Riches (1987-1988).Campbell kópa nínú àwọn fíú bí School Daze (1988), Rooflóúnjẹ (1989), Another 48 Hrsrs..
wikipedia
yo
Ó gba ìpèlórúkọ Ẹ̀bùn Independent Spirit Award for Best Supporting Female fún ìṣeré rẹ̀ nínú fíú Komedi ọdún 1990 tó ń jẹ́ House Party, ó tún kópa lẹ́yìn ná nínú apá kejì àti apá kẹta fíú ná; House Party 2 (1991), àti House Party 3 (1994).Lórí tẹlifísàn, Campbell ṣeré gẹ́gẹ́ bí G– Waters–Payne nínu eré Komedi Church Fox tó únjẹ Martin from 1992 to 1997 àti gẹ́gẹ́ bí Janet "Jay” Marie Johnson-Kyle nínú eré Komedi tẹlifísàn ABC tó ń jẹ́ my wife and Kids (2001-2005), èyí tó gba ẹ̀bùn NAACP Image Award for Outstanding Actress in a Comedy series fún..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ná ó tún kópa nínu àwọn eré tẹlifíṣàn bí Rita Rocks (Lifetime, 2008-2009), the protector (Lifetime, 2011), àti Dr..
wikipedia
yo
Ken (ABC, 2015–2017).Àwọn òṣèré fíújáde ara Américowon oṣere tẹlifísàn Ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Mosúnmọ́la Abudu, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Mo Abudu, tí ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ ògbóǹtarìgì agbóhùnsáfẹ́fẹ́, ẹlẹ́yinjú àánú, Onimọ̀ràn Ìṣàkóso àwọn òṣìṣẹ́ àti ẹni tí a mọ̀ mọ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Forbes fi mọ́ Abdul han gẹ́gẹ́ bíi obìnrin ilẹ̀ adúláwọ̀ tó lọ́lá jù lọ ni.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Abudu sí Hammersmith ní apá ìwọ̀-oòrùn ní London..
wikipedia
yo
Ó sì lọ sí Ridgeway School, midKent College àti West Kent College..
wikipedia
yo
O gboye master's degree ninu human Resource management ní London.Iṣẹ ti o yan laayoiṣẹ rẹ ni EbonyLife TV ni ọdun 2006,Abudu bẹrẹ EbonyLife TV, eto igbohunsafefe ti o tan ka orilẹ-ede to ju okandínláàádọ́ta lọ ni Ilẹ Awose ati ni UK ati Caribbean..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ètò kan lábẹ́ Media and Entertainment City Africa (Mec Africa)..
wikipedia
yo
EbonyLife TV wa ni Tinapa Resort ni Calabar, Ìpínlẹ̀ Cross Rivers, orile-ede Naijiria.Ni ọdun 2018, Sony Pictures Television (CO) kede Asese ifowosowopo ọlọ́dún mẹ́ta pẹlu EbonyLife TV ti o maa ni ṣe pẹ̀lú gbigbe fiimu The Dahomey warriors jade.Iṣẹ rẹ miiran; EbonyLife Films Abudu da EbonyLife Films silẹ..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Elfike ní ọdún 2016 láti gbé fíìmù The Wedding Party jáde.Momentsments with Moabudú jẹ́ olóòtú àti ẹni tó gbé ètò "Moments with mọ" kalẹ́ tí ó jẹ́ ètò ojoojúmọ́ àkọ́kọ́ tí ó hàn káàkiri ilẹ̀ adúláwọ̀ lórí afẹ́fẹ́.Ní ọdún kẹwàá ọdún 2009, a ti rí tó ìgbà ìgbà tí ètò tí ó gbé sórí afẹ́fẹ́ hàn lórí afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Àwọn ètò orí afẹ́fẹ́ náà máa ń dá lé lórí ìgbésí ayé ẹ̀dá, ètò-ìlera, àṣà, ètò-òṣèlú, eré-ìdárayá, iṣẹ́, orin àti ọ̀rọ̀ lórí ìgbéyàwó láàárín ẹ̀yà méjì..
wikipedia
yo
Wọ́n ti gbé àwọn olókìkí èèyàn lóríṣiríṣi, Ààrẹ orílẹ̀-èdè àti àwọn èèyàn tó lórúkọ sórí ètò náà.The débáterSabudu jẹ́ olùdásílẹ̀ àti ẹni tó gbé ètò The débáters jáde..
wikipedia
yo
O jẹ eto ti Guaranty Trust Bank n ṣakoso nipa eto Iṣuna..
wikipedia
yo
Ètò náà dá lé lórí “Fífún Ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní ohun kan” nípa gbígbé ọ̀rọ̀ sísọ lárugẹ.Àwọn àṣeyọrí rẹ̀ Forbes Africa fi Abudu hàn bíi obìnrin adúláwọ̀ àkọ́kọ́ láti ní Pan-Africa TV Channel ní ọdún 2013..
wikipedia
yo
Wọ́n ka a mọ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin mẹẹdọ́gbọ̀n tó lọ́lá jù lọ lórí Global TV láti ọwọ́ oníròyìn Hollywood ní ọdún 2013..
wikipedia
yo
and received the lépa of the year award by women sponsorship in New York (2014)..
wikipedia
yo
ní ọdún 2014, Babcock University da a lọ́lá pẹ̀lú Honorary Doctor ninu Humane Letters..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, wọ́n dá a lọ́lá pẹ̀lú dadav d'Honneur tí MiPTv 2019 ní Cannes, ìlú France..
wikipedia
yo
Èyí sì jẹ́ kó jẹ́ obìnrin ilẹ̀ adúláwọ̀ àkọ́kọ́ tó gba àmì ẹ̀yẹ náà..
wikipedia
yo
Bakan naa, won ka a mo okan lara ogorun-un obinrin ti o lola ju lo lori 2020 Powerlist ni UK lati ile Adulawo.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Angela Evelyn Bastt (Ọjọ́ìbí August 16, 1958) jẹ́ òṣèré àti alákitiyan ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíquire Ara Américo Òṣèré tẹlifíṣàn Ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
(; Ọjọ́ìbí September 4, 1960) jẹ́ aláwàdà, òṣèré, Olukọwe, ati atọ́kùn ará Amẹ́ríkà, àti ikan nínú àwọn ẹbí Wayan..
wikipedia
yo
Wayan sise bi alawada ati osere ni gbogbo odun awon Ẹ̀wádún 1980, nigba to kopa ninu ere alawada Saturday night live.ninu ere alawada in Living Color gangan ni ebun rẹ ti yo jade gege bi Olùkọ̀wé ati aláwàdà lati 1990 di 1992..
wikipedia
yo
Láti ìgbà ná ó ti kópa nínú fíú àti eré tẹlifísàn Ọ̀pọ̀lọpọ̀ bíi The Last Boy Scout àti Major Payne, àti eré tẹlifíṣàn my wife and Kids..
wikipedia
yo
Láti 2016 dé 2019, ó ṣeré gẹ́gẹ́bí Roger Murtaugh nínú eré Church Lethal Bvpọ.Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Amerikááwon osere agbọ̀n ará ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
tóótunÓ Hall (Ọjọ́ìbí February 12, 1956) jẹ́ aláwàdà, òṣèré, atọ́kùn ètò ìbánisọ̀rọ̀, kọ̀wé àti olóòtú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ nígbà tó ṣe atọ́kùn ètò The Anauo Hall show, ètò alẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ lórí agbọ̀n láti 1989 dé 1994, àti láti 2013 Dé 2014.Ìtọ́kasí ọmọ Áfríkà Américo fún òṣèré ará Kakàáwọ́n aláwàdà ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Deborah káyé Allen (ọjọ́ January 16, 1950) tó gbajúmọ̀ lásán bi Debbie Allen jẹ́ òṣèré, oníjó, olùkọ́-ijó, akọrin-akọ̀wé-orin, olùdarí, olóòtú ará Amẹ́ríkà, àti ọmọ ẹgbẹ́ tẹ́lẹ̀ President's Committee on the Arts and humanities..
wikipedia
yo
Wọ́n ti pe lórúkọ ní ìgbà ogun fún ẹ̀bùn Emmy (Ó gba ní ẹ̀mẹ́ta), ìgbà ìpàgọ́ fún ẹ̀bùn Tony, Be ni ó sì gba ẹ̀bùn Golden Globe ní ẹ̀kán, wọ́n sì fun ní ìràwọ̀ ní orí Hollywood Walk of Fame ní 1991.Allen gbajúmọ̀ fún eré rẹ̀ lórí eré orin-dírámà Church Fame (1982-1987), níbi tó ti ṣeré bi Lydia Grant, Olùkọ́ni-níjọ, ohun sí lọ ṣe olùkọ́-ìjọ àgbà fún eré tẹlifíṣàn ná..
wikipedia
yo
Fun iṣere yi ni 1983 o gba ẹbun Golden Globe and ẹbun Tony meji wọn si pelorukọ fun ẹbun Emmy mẹrin..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn na Allen ṣiṣẹ́ bí olùdarí àti olóòtú, níbi tó ti ṣe olóòtú àti olùdarí eré ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ 83 nínu 144 fún eré Komedi NBC a different World (1988-1993)..
wikipedia
yo
Ó padà sí níṣeré ngba tó kópa nínú eré tẹlifíṣàn NBC in the House láti 1995 di 1996, àti láti 2011 ó bẹ̀rẹ̀ síní ṣeré bí Dr..
wikipedia
yo
Catherine Avery nínu eré dírámà ilé-iwosan ABC Grey's Anatomy níbi tó tún ti ṣiṣẹ́ bí olóòtú àgbà àti olùdarí..
wikipedia
yo
Ní 2001, Allen sí ilé-ẹ̀kọ́ ìkójọ Debbie Allen dance Academy ní Los Angeles, California..
wikipedia
yo
Ohun ni aburo Analelicia Rshad ti ohun na je akorin, osere ati oludari.Awon itọkasiàwọn oṣere ara Ameria omo Afrika Amẹrika..
wikipedia
yo
"Aparthood") ni Siste Ijoba Iṣẹgbéraga awon oyinbo to da lori iyasọ́tọ̀ọ̀tọ̀ Ẹya ti Awọn oyinbo fi tipátipá fi lati dinku ni orile-ede Afrika ati South West Africa (ti a mo si Namibia loni) lati odun 1948 titi di 1994 Apaceidi je ijoba tipátipá to da lori Baass (SS (Moko awon oyinbo), to mu daju pe awọn oyinbo, Euro, Onibo pe pe iye won ko po, gaba le ori gbogbo eniyan ni orile-ede guusu ninu oselu, awujo ati oko..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Siste awọn oyinbo yi ṣe to, awọn oyinbo ni wọn gbúdọ̀ siwaju ni gbogbo igba, awọn ọmọ ara Asia tẹ̀ lé wọn, bẹ sìni awọn Aláwọ̀dúdú ara Afrika lo gbọdọ gbẹ̀yìn..
wikipedia
yo
The Economic Legacy and Social effects of àpartheid continue to the present Day.Ìtọ́kasísing Juitan ilẹ̀ gúúsù Áfríkàise awon oyinboapa Gìpíndọ́gba ní orilẹ-ede gúùise Afrika awon oyinbo ni Afrika..
wikipedia
yo
Akinlóyè akínyẹmí, (1954-2012), tí wọ́n tún mọ̀ sí Sergeant Carter, jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó dé ipò àṣẹ Major nínú iṣẹ́ ológun orí-ilé ṣaájú kí ó tó Fẹ̀yìn Tì..
wikipedia
yo
O jẹ okan lara awon afẹ̀sùnkan nipa ìdìtẹ̀ gbàjọba,ti won si fi sẹ́wọ̀n laarin odun 1987 ati 1995..
wikipedia
yo
Lásìkò ti wà níbi iṣẹ́ ológun, ó ṣiṣẹ́ lábẹ́ ilé iṣẹ́ ti (Nigerian Army signal Corps)..
wikipedia
yo
Oun ni aburo fun Ọ̀gbẹ́ni Bọlaji akínyẹmí.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati Èkó reakinYemi jẹ ọmọ bibi Ilu Iléṣà, ni ìpínlẹ̀ Osun..
wikipedia
yo
Oló sí ilé-ẹ̀kọ́ Government College tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn kí ó tó tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ ti Ìkẹ́kọ̀ọ́ ti Ìgọ́ra àwọn ọmọ ológun Igbó ní Ìlú Igbó Ọ̀rá ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní àsìkò ọdún 1960..
wikipedia
yo