cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Iṣẹ́ ààyè òdodo ni láti kópa nínú àtúnbí nípa wíwá ọ̀nà láti mú omiẹ̀pọ́n wá bá àwọn ẹ̀yìn... | wikipedia | yo |
Tòkè Makinde (bíi ní ọjọ́ kẹta Oṣù ọkànlá ọdún 1984) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ adarí ètò ọkọ̀ òwúrọ̀ ní orí 93.7 FM.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí tòkè Mali wà ní ọjọ́ kẹta oṣù Kọkànlá ọdún 1984 sí ìlú Èkó ní Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O lo si ile eko Federal Government Girls College ni iluOyo, Ibadan Lomakin lo si ile eko giga ti University of Lagos ni ibi ti o ti ka English and literature.ise ni odun 2010, Makinde koko fi ara re han ni ori ero agbóhùn si afẹfẹ ti RyOHÙN 93.7 FM ni ori eto oko Owuro.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2012, ó ṣe atọ́kùn ètò obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun pẹlu Tosyn Bucknor ati tọ́ka àwọnd jọ ṣe atọ́kùn fún ètò flytime TV's live chicks.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2012 yi naa ni o beere eto Toke Moments ni ori YouTube vlog.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, hip hop World Wide Magazine kede Makinde gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àti ọ̀rọ̀ ilé iṣẹ́ wọn.. | wikipedia | yo |
O gba iṣẹ gẹgẹbi ikan lara awọn atọkun eto ni ilu ise Ebony TV fun eto Moments.Makinde ti ṣe atọ́kùn ẹtọ fun ọpọlọpọ eto bii Future and City People Award ni ọdun 2013 ati Headies Award ni ọdun 2014.. | wikipedia | yo |
Makinde kọ ìwé on Becoming ní Oṣù kọkànlá ọdún 2016.. | wikipedia | yo |
Ìwé ná sọ̀rọ̀ nípa ìṣòro tí ó ní àti ti ọkọ rẹ̀ ṣe já kù n lé.. | wikipedia | yo |
Makinde ló ká kiri àwọn ìlú bí South Áfríkà, U.S.A.A, U.K àti àwọn ìlú mìíràn ní ilẹ̀ Áfíríkà láti ta ìwé náà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ó tún kọ ìwé mìíràn tí ó pe àrírí rẹ̀ ní Handbag Line.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2013, Makindewa jẹ aṣoju fun ile ise United Africa company of Nigeria, oun pelu Osas Ighodárò, Dare Art Alade, ati Dan Foster.Ile ise Olowo iyebiye ti Nestle ni ipinle Naijiria fi se oju oja Maggi.Ni ọdun 2016, o di aṣoju fun ile ise MeCran Cosmetics.. | wikipedia | yo |
Òun sì ni aṣojú fún ilé iṣẹ́ payPorte àti CiroC.Aiyé rẹ̀ Makindewá ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màjẹ àyídà ní ọjọ́ karùn dínlógún oṣù kìíní ọdún 2014, olólùfẹ́ rẹ̀ fún ọdún mẹ́jọ.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, ó pínyà pẹ̀lú àyídà lẹ́yìn tí ó rí wípé ó ti fún ẹlòmiràn lóyún.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ karùn oṣù kẹwá ní ilé ẹjọ́ tún ìgbéyàwó náà kà ní ìpínlẹ̀ Èkó lórí pé àyídà ṣe àgbèrè.Ìkójiwèéàwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àlùàlùrin jẹ́ irú ohun ọ̀gbìn kan pẹ̀lú orúkọ sáyẹ́ńsì Allium Cepa (ní èdè Latini).. | wikipedia | yo |
Àlùàlùbò jẹ́ ewébẹ̀ tí ewé ati kókó rẹ̀, tí a dà wọ́n mọ̀ pẹlu òórùn ati ìta wọn, ṣé ẹ jẹ bíi àwọn ọ̀gbìn.. | wikipedia | yo |
Captain Josephine Okwuth tolè ti a bi ni ojo karun-un osu keji odun 1931 je omo bibi orile-ede Naijiria ati oṣiṣẹbinrin akọkọ ti a fun láṣẹ lati je adari ati ogagun keji ninu ẹgbẹ Igbimọ Ile ileNaijiria.igbesi Naijiria.Igbesi ati eto-ẹkọ rẹ-un Oṣu-un Oṣu Keji ni a bi a bi Josephine ni Oroko- to wa ni apa guusu ni Ipinle Delta.. | wikipedia | yo |
O ṣe idanwo fun iwe-ẹri ti University of Cambridge ni ọdun 1950.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí ilé-ìwé àwọn agbẹ̀bí midWives Training College, High Coombe ní Surrey ní United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Ó sì jáde ní ilé-ìwé náà bi nọ́ọ̀sì tí ó forúkọ sílẹ̀ tí ó wà lábẹ́ General Nursing Council fún England àti Wales ní oṣù kẹjọ ọdún 1956.. | wikipedia | yo |
Central midWives Board of England si gba a wole lati sise ni ojo kokanlelogbon osu kejila odun 1961.Iṣẹ to yan laayoJosephine je nọọsi akosemose amo o pinnu lati dara pọ mo Igbimọ ologun ti ile Naijiria nitori Ife to ni si awon obinrin ti o wa lara Igbimọ ologun Ile Britain ati pe o wun un lati ja fun orile-ede re.leyin ti o dara po mo igbimo naa, won yan an sipo ogagun keji ni odun 1961.. | wikipedia | yo |
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n gbóríyìn fún, òun àti àwọn obìnrin yòókù tí ó wà ní ìgbìmọ̀ ológun náà ń kojú ìgbéníjà lóríṣiríṣi láti ọ̀dọ̀ àwọn ọkùnrin tó jọ ń ṣiṣẹ́ pọ̀.. | wikipedia | yo |
Ni ojo karun-un ọdun 1967, o gba ìfẹ̀yìntì fúnra rẹ.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2014, arabinrin naa di Oloogbe.àwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
O gba ebun agbóhùnsáfẹ́fẹ́ to tayo julo ni apa iwo guusu ni Nigerian Broadcasters Merit Awards ni odun 2016.ibẹrẹ aye ati eto-ẹkọ rẹ won bi Mordi si Ilu Port Harcourt, Rivers State ni Ipinle Naijiria.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ikú bàbá rẹ̀, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Nigeria, Nsukka lati ka iwe ìmọ̀ ogun ṣùgbọ́n ó kúrò láì parí nitori ìyọnu ìbálòpọ̀ ti ó rí lati ọwọ́ ikan lára àwọn olùkọ́ rẹ̀.Iṣẹ́ kíkí jẹ́ oníròyìn,agbóhùnsáfẹ́fẹ́, òṣèré àti òǹkọ̀wé ni ìlú Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun sì ni ojú oníròyìn fún BBC, òun pẹ̀lú sì ní olórí adarí ètò fún WFM 91.7 .. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2017, o beere fun ida duro ìyànjẹ awon olopa eyi ti o waye leyin igba ti awon olopa ko ohun ati ololufe re, ti won si fi esun pe won se egbe òkunkun.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2015, wọ́n fà kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹ̀yàn ti ọjọ́ ọ̀la rẹ̀ dára jùlọ fún àwọn Ọ̀dọ́mọdé Oniròyìn ní Nigerian Broadcasters Merit Awards.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, ó gba ẹbùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó tayọ jùlọ ní iwo guusu ní Nigerian Broadcasters Merit Awards.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fa kalẹ̀ fún agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Obi ní SRERE All-Youth Awards.. | wikipedia | yo |
Ni ojo keta osu kokanla odun 2019, won fa kale fun ebun ojo iwaju ti ile Afrika fun Aye awon oniroyin.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe fíìmù Life at the Bay ní ìlú Èkó ní ọdún 2019.Ó tú àṣírí àwọn olùkọ́ tí wọ́n fi àìpo ní àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin lára ní ọjọ́ keje oṣù kẹwàá ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Ile eko giga ti University of Lagos ati University of Ghana ni awon oluko yi wa.. | wikipedia | yo |
BoniBonice Igbeneghu ti University of Lagos, Dr rans Gyampo ati Dr.. | wikipedia | yo |
Paul Kwame butako ti University of Ghana ni awon olukọ ti asiri won tu ni aworan ti Mordi se.. | wikipedia | yo |
Boniojúce kúrò ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Lagos, wọ́n tún yọ kúró nínú ipò àlùfáà ní ilé ìjọ ti FourSquare Gospel Church.. | wikipedia | yo |
Asiri yí ná ni ó fã tí wọ́n fi ti yàrá tútù tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Lagos.. | wikipedia | yo |
Olórin gbajúmọ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Adekunle Gold júbà Iṣẹ́ tí Mordi ṣe.. | wikipedia | yo |
Igbá kejì adarí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí, Atiku Abubakar gba àwọn ìjọba ní ìmọ̀ràn pé kí wón ṣe àmójútó àwọn ìwà ìbàjẹ́ àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga.. | wikipedia | yo |
Ninu ọ̀rọ̀ ti Mordi sọ fun àwọn Sahara Reporters, o ni wipe oun ti gba awon ipe lowo awon eyan ti won si so wi pe awon ma se ijamba fun leyin igba ti o tu asiri naa si ita.Ni ojo kesan osu kewa odun 2019, Mordi ati awon eyan re fi fiimu ti o wo wakati kan kale.. | wikipedia | yo |
Fíìmù yìí sọ̀rọ̀ nípa àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga tí wọ́n dáwá fún ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìrin, èyí ló tún ṣe Okùnfa tí wọ́n ṣe dá Dr.. | wikipedia | yo |
Samuel Oladipo duro lẹnu ise ni University of Lagos.. | wikipedia | yo |
Ọjọ́ yí náà ni ìjọba ṣe òfin tuntun tí ó lòdì sí ìbálòpọ̀ olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́.Àwọn ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
kádària Ahmed ti i se omo bibi orile-ede Naijiria je akoroyin, onisowo ìgbéròyìnjade ati olugbalejo lori rékọjá.. | wikipedia | yo |
O si ti sise ni ile-ise nsejade, redio, yaya ati awọn awujọ arabinrinjade lori ero ayelujara.igbesi aye ati iṣe to yan laayo Ahmed gboye ma ninu Television ni GoldSmiths, University of London, ati Bachelor's ni Bakokoro University Kano.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ Chevening Scholar.O bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tó yàn laayo ní BBC níbi tí ó ti jẹ́ olóòtú àgbà tó ń ṣiṣẹ́ lóri àwọn ètò bíi Focus on Africa àti Network Africa tó ń gba àmì-ẹ̀yẹ lóríṣiríṣi.. | wikipedia | yo |
Nígbà tó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Alátùnnko fún Next (Nigeria) èyí tí ó jẹ́ àgbéjáde-ìwé tó ń gba àmì-ẹ̀yẹ lórílórí.. | wikipedia | yo |
Níbẹ̀ ni ó ti mójú tó yàráìkọ̀ròyìn tó ní bíi ọgọ́fà èèyàn àti ọgbọ̀n òṣìṣẹ́ mìíràn láti jíròrò lórí ìsayé ìwé tó ń gbé jáde.. | wikipedia | yo |
Ilé-iṣẹ́ náà dáwọ́ ìgbéwèéjáde dúró ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2011.Ní ọdún 2011, ó ṣatòkùn ìtàkùrọ̀sọ láàárín àwọn olùdìbò fún ipò Ààrẹ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún náà.Ní ọdún 2014, ó sọloo straight talk tó jẹ́ ètò ìgbàlejò àwọn tó ń rí sí dídá ìpinnu lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ètò náà di ìlúmọ̀ọ́ká nígbà tí iye àwọn èèyàn tó ń wò ó ju mílíọ̀nù mẹ́rin lọ.. | wikipedia | yo |
Diẹ lara awọn eeyan to gba lalejo ti o si ni ifọrọwanilẹnuwo pẹlu wọn lori eto naa ni Ibrahim Babangida, tonye Princewill, Babatunde Fashola, Rotimi Amaechi, Ali Baba, Oby Ezekwesili.Ni ọdun 2017, o tọkàn tuntun kan the Core kalẹ̀ lori Channels TV.. | wikipedia | yo |
Ni osu July odun 2017, o ni ifọrọwanilẹnuwo pelu Nnamdi Kanu ti o je olori awon indigenous People of Biafra (ipob) ti o si n kede Biafra tabi iku.Ni igbaradi fun idibo odun 2019, o satókun Town Hall meeting fun awon oludibo fun ipo Aare ati Igbakeji won.lowolowo, Ahmed je okan lara awon igbimo onídàájọ́ fun Wole Soyinka Centre for investi5BFR Journalism ati okan lara awon igbimo olutọju ti Premium Times Centre for investi5BFR Journalism ati promásì Quill Awards.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ ọkan lara awọn Nigerian Guild of Editors ati Nigerian Institute of Directors.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ó dá Daria Media Ltd sílẹ̀, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó rí sí ìgbélárugẹ iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn.Iṣẹ́ rẹ̀ àwọn ìròyìn tí Ahmed ti kọ lórílériri ni wọ́n ti jáde ẹ̀ nínú àwọn ìwéìròyìn nílé wa àti lágbàáyé bíi Daily Trust, The Guardian, àti The Financial Times of London.Ó sì ti ṣàtúnkọ́ iṣẹ́ àgbéjáde méjì.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ ní Nigeria The Good News, ní ọdún 2012, ní ọdún 2014 Henrich BoEll Foundation fún láṣẹ láti ṣàjade ìwé tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ‘Lagos - a Clímate Resilient megacity'.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Judulge ṣoni "Justin" FASnù (; 19 February 1961 – 2 May 1998) je was an English agbabọọlu-ẹlẹ́sẹ̀ ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì to gba bọọlu larin ọdun 1978 titi di 1997.. | wikipedia | yo |
Ohun ni egbon John FAFANjijiji agbaboolu-ede ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì omo Yoruba.. | wikipedia | yo |
John FAFANAB (, Ọjọ́ìbí 18 September 1962) jẹ́ ọmọ bàbá Nàìjíríà àti ọmọ ìyá ara Guyana, tó gbá-bọ́ọ̀lù àti atọ́kùn ètò ètò tẹlifísàn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ohun ati Justin FAFAnu jẹ tẹ̀gbọ́n.Ìtọ́kasí agba bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará ará gésíàwọn ọmọ Yoruba.. | wikipedia | yo |
David Robert Joseph Beckham (; Born 2 May 1975) jẹ́ is an English former professional agbabọọlu-ẹlẹ́sẹ̀ ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì to ti feyinti.Ìtọ́kasí.Àwọn agbabọọlu-ẹlẹṣẹ̀ ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sìàwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
NáhZDu Olufemi Owaya tí wọ́n bí ní ọjọ́ kini oṣu karùn un ọdún 1960, jẹ́ Onímọ̀ nípa ètò ẹ̀kọ́ àti alákòóso àgbà tẹ́lẹ̀ rí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Adékúnlé Ajasin, tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ti Ìpínlẹ̀ Ondó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ile-eko agba ti ajo ti United State Transparency International Standard (U13– sọ wipe o wa lara awon ile-eko to peregede julo ni odun 2014, lasiko isakoso Femi Ososo.. | wikipedia | yo |
Olufemi Ososo nikan ni o je alákòóso agba ile-eko Fasiti ti won yan lo sibi ijiroro apapo orile-ede Naijiriati o waye lasiko isakoso Aare ribiribi Ebele Jonathan ni odun 2014.. | wikipedia | yo |
O gbs ipo aṣẹ alákòóso àgbà ile-ẹkọ Adekunle Ajasin ni Oṣu Kini ọdun 2010.. | wikipedia | yo |
O jẹ okan lara omo egbe ajo African and African-American Studies associate, at Harvard University, Cambridge, MA, USA.Awon itọka síàwọn ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
DWayne Douglas Johnson (Ọjọ́ìbí May 2, 1972), To tún gbajúmọ̀ pèlú orúkọ ìjàẹmu rẹ̀ The Rock, jẹ́ òṣèré, olóòtú, oníṣòwò, Ajáẹmu tician àti agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ti Amẹ́ríkà ará Amẹ́ríkà .. | wikipedia | yo |
O jẹ ajaẹmu fun ile-ise World WW Federation (WWW, loni bi WJI) fun odun mejo ko di osere osere.. | wikipedia | yo |
Àwọn fí53 rẹ̀ ti pawó tó tó ní Amẹ́ríkà àti lagbaye, tó sọ di ikan nínú àwọn òṣèré tó pawó fíú ní gbogbo ìgbà ìdì ìÌtọ́kasí. àwọn òṣèré fífi ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
OloyeMargaret Ekpo ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínogun oṣù kẹsan an ọdún 1914, jẹ́ ajàfẹ́tọ́ àwọn obinrin olùkérò-jo,ati olùfilole Ìkópa àwọn obìnrin nínú ìṣèlú àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì àti olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ ajìjà-n-gbara àwọn obìnrin tó gbé àsíá ìṣọ̀kan ẹ̀yà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dání.. | wikipedia | yo |
O sise ribi ribi paa paa julo ninu igbara ominira orile-ede Naijiria kuro lowo awon oyinbo amunisin.. | wikipedia | yo |
Oun ni o lewaju ninu itapórógan ti o fa faaka to waye laarin ṣiṣan owo-ori okunrin ati obinrin ni ilu Aba (aba women's Riot) ni apa ila-oorun orile-ede Naijiria.Awon itọka.. si.. | wikipedia | yo |
OLUWAkàkà Ogunseye tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ akọ̀ròyìn, Asatun àti àyẹ̀wò àkọsílẹ̀, àti adarí iṣẹ́ tó rí sí èdè ti West Africa ni BBC World Service.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ asatunkọ ìwé-ìròyìn The Punch Newspaper nígbà kan rí.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ ọkan lara àwọn Mandela Washington Fellow.igbesi ayé ati ètò-ẹkọ rẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni a bi Ogunseye si, si ẹya Yoruba.. | wikipedia | yo |
University of Lagos ni ó ti gboye Bachelor's degree ninu Biochemistry, leyin naa ni o gboye post-graduate diploma ninu Print Journalism ní Nigerian Institute of Journalism.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010, ó gboyè Masters degree nínú Media and Communications ní Pan-Atlantic University.. | wikipedia | yo |
Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó ń kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Leicester, United Kingdom láti gboyè PhD nínú Politics and International Relations.Iṣẹ́ tó yàn ìyò Ogunseye bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akọ̀ròyìn Látìgbà tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́dún kejì ní University of Lagos tó ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa Biochemistry.. | wikipedia | yo |
Musa egbemana lo to sọ́nà bi won se n ṣàkọsílẹ̀ iroyin ati awon isele ni University of Lagos ti won maa ṣàgbéjade lori iwe-iroyin the sun newspaper Nigba ti Femi Adeṣina je Asatun iroyin ni odun 2004.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí News Star Newspaper gẹ́gẹ́ bíi Senior Correspondent ní ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, ó dara pọ̀ mọ́ The Punch Newspaper gẹ́gẹ́ bíi olùrànlọ́wọ́ Asatun ìròyìn àti ìròyìn lórí òsèlú títí di ọdún 2012.. | wikipedia | yo |
Rẹ̀sín ti jẹ́ akọ̀ròyìn láti ọdún 2006 kí ó tó di àṣàtúnkọ ìròyìn.. | wikipedia | yo |
Ó ṣiṣẹ́ fún Sunday Punch gẹ́gẹ́ bíi Aàṣàtun ìròyìn àti Senior Correspondent tó ń ṣiṣẹ́ lórí ìwà ọ̀bàyéjẹ́ nílé wa àti lágbàáyé.. | wikipedia | yo |
Rkún ni Asatun iroyin akoko to je obinrin ati eni to kere ju lo ni The Punch Newspaper.Awon ami-eye reOgunseye ti gba ami-eye lóríṣiríṣi to n lo bii marun-ààbò.. | wikipedia | yo |
Cartúndé adébọ̀wálé David tí orúkọ ìnági rẹ̀ jẹ́ llọ́ 1 jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun si ni atọkun eto oga Madam lori Wazobia FM 94.1.ibẹrẹṣe aye ati eto-ẹkọ rẹ Cartúndé lọ si Ile Eko ti Ijebu-Ode Anglican Girls Secondary School.. | wikipedia | yo |
O ka iwe imo ofin ni ile eko giga ti Lagos State University.Iṣẹ Ọmọ́túndé bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ise gege bi agbejoro ni odun 2000.. | wikipedia | yo |
O sise ni ile ise ofin titi di odun 2004 ti o wa pada wa di agbóhùnsáfẹ́fẹ́.. | wikipedia | yo |
Ọmọ́túndé ma ń kópa nínú eré ífara ṣíṣe pàápàá ti èdè òyìnbó àti Yorùbá.Ó kópa nínu eré Jenifa's Diary, ní ibi tí ó ti ṣe adákú.. | wikipedia | yo |
Ó kọ́kọ́ sọ̀rọ̀ lórí afẹ́fẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ìgbà tó dára pọ̀ mọ́ Metro FM.. | wikipedia | yo |
O pada wa dara po mo Wazobia FM ki o to kuro ni ọdun 2019 leyin ti o ti lo kọja ọdun mọkanla pẹlu wọn.. | wikipedia | yo |
Ọmọ́túndé ṣe eré àkọ́kọ́ títí ẹ jáde ní ọdún 2020, èyí tí ó pe àkòrí rẹ̀ ní When Love Is Not Enough.. | wikipedia | yo |
ó gba orúkọ ínági rẹ̀ ní orí ètò kan nínú ètò kan tí ó ti ń ṣe atọ́kùn.. | wikipedia | yo |
O sọ fun awon eyan ki won fun oun ni oruko inagi, ninu oruko ti awon eeyan fun, nibẹ ni o ti wa mu lòlò 1.Ni osu keje odun 2017, La Mode Magazine fi se oju iwe akoko won.Ẹ̀yà ara iwe irohin iwe irohin la Mode ti o kẹhin jẹ ìkọjá pẹlu Chika Ike, ṣugbọn Ọran lọwọlọwọ yii paapaa gbóna! Oro tuntun yii jẹ gbogbo nipa ẹwa, agbara, ati awọn igun ati awọn ẹya ara ẹrọ iṣowo njagun temi Aboderin-Alao ati eniyan redio Oguntúndé Adébọ̀wálé David ti a n pe ni Llòlò-ẹbun Ọmọ́túndé gba ẹbun agbóhùnsáfẹ́fẹ́ to tayọ julọ ni Eko lati ọwọ́ Nigerian Broadcasters Merit Awards.Ayé rẹ Ọmọ́túndé jẹ iya ọmọ mẹrin, ọkunrin mẹta ati obinrin kan.. | wikipedia | yo |
Kò sí pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ mọ́.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Dídi Akinyelurẹ̀ jẹ́ akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Britain tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ lórílórí.. | wikipedia | yo |