cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
University of Nottingham ni o ti kẹkọọ jade lori Chemical Engineering..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Keje ọdún 2016, ó gba àmì-ẹ̀yẹ BBC World News Kookel Dumor..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016 bákan náà, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Special Excellence alumni Laureate ti University of Nottingham..
wikipedia
yo
Dídì ni wọ́n lọ fún ojú CNBC Africa's Live Morning Show Open Exchange ti West Africa.eto-ẹkọ ati Iṣẹ to yan laayodídì jẹ akọ̀ròyìn tó ti ní ọ̀pọ̀ ìrírí látàrí iṣẹ́ ṣíṣe rẹ̀ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Ìgbéròyìn jáde lórí..
wikipedia
yo
O ti sise atọkun, olootu, ati àtúnkọ iroyin lori redio ati ẹgbaa fun iroyin lori BBC News Lhamu Mẹ́wàá, BBC World News, BBC World Service, BBC Focus on Africa, BBC Business Daily, BBC Newsday, ati BBC Radio 4..
wikipedia
yo
Iṣe rẹ lori eto iṣowo fun obinrin wa lara iṣẹ ti World Bank yan fun ami-eye Women Entrepreneurship ]ting Category ni One World Media lodun 2018.O ti han lori Forbes Africa Magazine, o si wa lara awọn akoroyin lobinrin to lola ju lọ lágbàáyé. O je onisowo ero ìgbéròyìn jade latari eto ori afefe a place in Africa to da sile..
wikipedia
yo
Ó tún ṣagbátẹrù reap, ètò kan lórí ẹ̀rọ ìgbéròyìn jáde..
wikipedia
yo
Dídi n ṣiṣẹ́ ribiribi nínú iṣẹ́ tó yàn láàyò gẹ́gẹ́ bíi olóòtú àti adarí ètò láyéye..
wikipedia
yo
Ní oṣù karùn-ún ọdún 2019, ó ṣagbátẹrù ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn èèyàn ńláńlá ní United Nations ní Geneva..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìgbìmọ̀ Adájọ́ náà ní Dame Wendy Hall, Nobel Laureate, Prof. Carlo Rubíà àti Prof..
wikipedia
yo
Jürgen Schmidhuber. Ní ọdún 2018, ó ṣagbátẹrù ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò lórí United Nations pẹ̀lú sir Roger PenRose àti Nobel Laureate Jacques Dubochet.Ó tún jẹ́ olóòtú ètò Africa CEO Forum àti olóòtú fún ayẹyẹ Africa CEO Awards and Gala Dinner..
wikipedia
yo
O ṣagbátẹrù ètò kan lórí òwò ṣíṣe ní London Business School fún Africa Summit, àti Future Energy Africa Exhibition and Conference ní Cape Town, South Africa.O dari ètò BBC Africa debate on FAke News ní Màláwì àti The BBC Women in Digital Journalism Panel fún ayẹyẹ ọ̀sẹ̀ ìgbéròyìn jáde lórí ayélujára ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O tun soloo Africa Summit fun University of Nottingham, the Future hi Exhibition and Conference, The West Africa Property Investment Summit, The ‘Lagos at 50’ International Conference ati The Lagos Kano Economic Summit..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kesàn-án ọdún 2017, United Nations pe ojú láti ní ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn èèyàn ní un Convention to Combat Desertion ní Oros ìlú China.Dídì ti ní ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olóṣèlú ńláǹlà àti adarí iṣẹ́ lórí.Kò tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn, ó ti ṣiṣẹ́ ní Barclays Wealth ní ìlú London.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Denrele Adémikítan Obasa (1878-1948), jẹ́ ọmọ bíbí Ilé-Ifẹ̀ àmọ́ tí ó fi ìlú Èkó ṣe ibùgbé..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn akéwì ilẹ̀ Yorùbá lásìkò ọdún 1920s..
wikipedia
yo
Òun ni olóòtú àgbà fún ìwé -ìròyìn ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀, tí ó ń gbé jáde pẹ̀lú èdè oríṣi méjì, tí ìwé-ìròyìn náà sì jẹ́ ẹ̀kejì irú rẹ̀ tí yóó ma Djíkun lédè abí.Ìbẹ̀rẹ̀ àyè kòpò bí Denrele ní ìlú ilé-Ifẹ̀, amo tí ó fi ìlú Èkó ṣe ibùgbé..
wikipedia
yo
O fìgbà kan ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí kanlẹ̀ kanlẹ̀ ṣáájú kí o tó kọ́ṣẹ́ ìwé títẹ̀ tí o sì tún dara pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé Padelwald Zchonis..
wikipedia
yo
Obasa padà dá ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé tirẹ̀ sílẹ̀ tí ó pè ní Iilarẹ̀..
wikipedia
yo
Ilé iṣẹ́ẹ ìtẹ̀wé rẹ̀ yí ni ó fún ní ànfàní láti tẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ oníyebíye rẹ̀ jáde pẹ̀lú ìrọ̀rùn..
wikipedia
yo
Chikaọdìn Sandra Oduah tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kẹta ọdún 1986 jẹ́ akọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìlú America tí ó sì jẹ́ olóòtú ìròyìn lórí afẹ́fẹ́, akọ̀wé, akọ̀wé..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ CNN Multichoice African Journalists Award ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Látàrí ipa tó kó lórí ìròyìn àwọn ọmọ Chibok ti Boko Haram gbé pamọ́..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akọ̀ròyìn lágbàáyé láti lọ sí ìlú náà ní apá àríwá - ìlà oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Akitiyan rẹ̀ náà ló mú gba àmì-ẹ̀yẹ ti Trust Women journalist of the Year láti ọwọ́ Thomson Reuters Foundation ní ọdún 2014.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rèéya igbó ní Odùah ti wá..
wikipedia
yo
Oun lo dagba jù lọ láàárín ọmọ meje ti àwọn òbí rẹ bi..
wikipedia
yo
Emmanuel àti Mercy Oduah ni ojo kerinla osu keta odun 1986 ni ogbaru nílùú Anambra State..
wikipedia
yo
Ó sì tẹ̀lé àwọn òbí rẹ̀ nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méjì tí wọ́n kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti lọ sí Metro Atlanta ní United States..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ ìwé-ìròyìn Vox nígbà tí ó wà nílé ìwé.Ní ọdún 2004, Oduah ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Center for Pan-Asian Community Services ni Dorast, Georgia níbí tí ó ti ń kọ́ àwọn ọmọdébìnrin tí wọ́n sá dédé fún ẹ̀mí wọn láti Sudan, Afghanistan, Liberia, Iraq, Bosnia, Rwanda àti South Sudan..
wikipedia
yo
Láàárín ọdún 2004 sí 2008, ó lọ sí Georgia State University níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa fíìmù, Anthropọlọgy àti Broadcast Journalism tí ó sì ti gboyè Bachelor of Arts degree nínú Anthrogy àti Bachelor of Arts degree Kejì nínú tẹ́lẹ̀Communications..
wikipedia
yo
Nígbà tó wà ní GEORGIA state University, òun ní ìigbakeji ààrẹ fún University’s Chapter of the society for professional Journalists..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Medill School of Journalism nígbà kan rí níbi tó ti gboye master of Science degree lọ́dún 2010 lẹ́yìn tó KẸ́KỌ̀Ọ́ lórí Broadcast Journalism.iṣẹ́ tó yàn làní ọdún 2009, ó ṣiṣẹ́ ayàwòrán nílùú Atlanta ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akàròyìn lórí afẹfẹ àti olóòtú agbeto sori afẹ́fẹ́ fún K24 ní Nairobi, Kenya níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ fún Jeff Kofin lọ́è 2010..
wikipedia
yo
Ó tún ṣiṣẹ́ fún National Broadcasting Corporation àti Sahara Reporters gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn.Òdúah padà sórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2012, ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akọ̀ròyìn àti agbéròyìnjáde lórí afẹ́fẹ́ tí ó dá dúró fún Al Jazeera..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ akọ̀ròyìn fún Voice of America àti English language Channel fún France 24..
wikipedia
yo
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò rẹ̀ pẹ̀lú ìlúmọ̀ọ́ká olórin d'Banj fún Sahara TV jẹ́ èyí tí ọ̀pọ̀ èèyàn wò tí ó sì bí ẹ̀rọ lórílériri..
wikipedia
yo
Wọ́n ti ṣàgbéjade ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ Chika Oduah sí orí ẹ̀rọ Ìgbéròyìn lórílẹ̀ bíi New York Times, The Guardian, Al Jazeera, The Daily Beast, CNN àti The Huffington Post.Ní ọdún 2014, Oduah di ìlúmọ̀ọ́ká látàrí iṣẹ́ tó se lóri àwọn ọmọ Chibok tí wọ́n gbé pa mọ́, èyí sì mú gba àmì-ẹ̀yẹ ti Trust Women fún journalist of the Year Award lati owo Thomson Reuters Foundation..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn àgbéjáde iṣẹ́ rẹ̀ lórí The Atlantic tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ in the land of Nigeria's Kidnapped Girls ló mú gba àmì-ẹ̀yẹ Livington Awards for Young Journalists lọ́dún 2015.ààtò àwọn àmì-èye rẹ̀òun ló gba àmì-ẹ̀yẹ African story Challenge Award lọ́dún 2015 láti ọwọ́ African Media Initiative àti International Center for Journalists látàrí iṣẹ́ rẹ̀ lórí ìtànkálẹ̀ májèlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Èyí náà ló bí àmì-ẹ̀yẹ dow Technology & Innovation Riviting Award ní CNN Multichoice African journalist Awards lọ́dún 2016..
wikipedia
yo
Ni ojo kejo osu keta odun 2016, o wa lara awon obinrin ti YNaija ka kun ogorun-un obinrin ti aye won wunni..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Percy Qgenza Award, èyí tó jẹ́ àmì-ẹ̀yẹ ìọdọọdún ti The National Association of Black Journalists ní United States máa n fún àwọn akọ̀ròyìn tó tayọ tó sì ní ní Ẹmi Qọ̀bọza.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Yéwándé Akinọ tí a bí ní ọdún 1984 jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ àgbà tó ń ṣiṣẹ́ lórí ìpèsè omi..
wikipedia
yo
O ń ṣiṣẹ́ fún ing o'rourd gẹ́gẹ́ bíi PricINC Geer 🙂 🙂
wikipedia
yo
Ó sì máa ń sóloo ètò orí afẹ́fẹ́ kan lórí ìmọ̀ ẹ̀rọ ni Channel 4 àti National Geographic.Ẹ̀tọ́-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọdún 1984 ni a bí Akinra sórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
M Akinola, tí ó jẹ́ Permanent secretary ti orílẹ̀-èdè Nàíjíríà nígbà kan rí..
wikipedia
yo
Akinola kẹ́kọ̀ọ́ lóri Engineering Design and appropriate Technology ní University of Warwick tí ó parí ní ọdún 2007..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó sì wà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó jẹ́ Mechanical Brasil fún Thames Water..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, ilé-iṣẹ́ Arup gbá a ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Design Ṣebíeer..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó jẹ́ adájọ́ fún ètò Queen Elizabeth prize for Engineering lọ́dún 2012 bákan náà, ó wà lára àwọn tí wọ́n yàn fún Iet Young Woman Gonest of the Year Award, oùn sì ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ náà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2014, Akinola ṣe Rainwater Fiyìn System.Ni ọdun 2013, Akinola sise pelu girl Guiding ni UK lati gba awon ọdọmọbinrin níyànjú ki won je onimo ero..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣàfihàn Akinola nínú ìkéde "Mietín tó Inspirẹ̀" ti Royal Academy of Engineering..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ṣàfihàn rẹ̀ nínu ìkéde "Fori the Future" tí QePrize lọ́dún 2014..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n pè láti sọ̀rọ̀ ní ayẹyẹ ti Ada Lovelace lọ́dún 2016..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ nínú ìdí "Portrait of an Ṣebíeer" ti Institution of Engineering and Technology dún 2017.ààtò àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó ti gba 1998 – Nigerian National AcẸwàwe Award - UK's Society of Public Health Gámónì Award for Young Rising Star Star- Exceptional Achiever Award by the Association for Black PaÌdíléÌdílé (AF-G) - Young Woman Geer of the Year From the Ietr - Management the's Top 35 Women under 35 - Precious Award for tòótọ́ woman in stem in Münster..
wikipedia
yo
Ire Aderinokun tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ Front End developer àti Google developer expert. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ nílẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ Google developer expert.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ire wá láti ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Olúnfún Aderinokun.Lẹ́yìn tó gba ìwé-ẹ̀rí onípele àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó lọ sí University of Bristol níbi tó ti gboyè Kóglors degree nínú experimental psychology..
wikipedia
yo
Nígbà tó ń kẹ́kọ̀ọ́ láti gboyè Masters degree nínú Law ní University of Bristol, Ifẹ̀ tó ní sí computer Science ló mú lọ sí CodeaỌ̀laọlá.Ire jẹ́ Ìpéjọjìyà developer àti USser Interface Desiner..
wikipedia
yo
Ire da blog ti re sile lodun 2015 ti o pe ni bitìbàdícode, ibè lo ti n da awon eeyan to nifee si imo komputa lẹ́kọ̀ọ́.Iṣẹ to yan laayo ire je Google developer expert to n sise lori front-End Techologist html, CSS, ati JavasCripaPT..
wikipedia
yo
Ó sákúwáyé ètò Frontstack, fún Front-End Engineering ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì tún bẹ̀rẹ̀ ètò scholarship kékeré kan láti fi rán àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n lè lọ fún Udácity Nanode ni Ẹ̀ka tó ní ṣe pẹ̀lú Technology tó wun wọn..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti igbákejì Ààrẹ fún Engineering of Buycoins.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sugar Ray Robinson (Orúkọ àbísọ Walker Smith Jr.; May 3, 1921 – April 12, 1989) jẹ́ Oníṣẹ́ Ìjàese ará Amẹ́ríkà tó jìjàdù láti ọdún 1940 di 1965..
wikipedia
yo
ìdùbú ti Robinson ta ninu awọn ẹka Welterweight ati Middightight mu ki awon oniroyin ereidaraya o da itoso to un je "pound for pound" (ese si ese), nibi ti won ti se iwera awon ajaese si ara won láìka ẹka agbara won..
wikipedia
yo
Wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sí inú ilé olókìkí ìjàese àgbáyé ní 1990..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ awon eniyan ni won gba Robinson gegebi Ajaese eninla to parun julo ni gbogbo igba aye, be e si ni ni odun 2002, iwe-iroyin The Ring fi Robinson si ipo kinni ninu atojo ti won se fun "80 Best fighters of the Last 80 Years" (Awon Ajaese Aroko 80 ti odun 80 tokọja).Àwọn Ajese ara Amerika..
wikipedia
yo
Funke egbemọdé tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ akọ̀ròyìn, olùdarí àti asatunko àgbà fún Daily Telegraph Publishing Ltd..
wikipedia
yo
Òun sì ni Ààrẹ Ana Takópa Guild of Editors.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni a bi Funke si..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Baptist Pdsingsing Primary School, ní iwo ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun..
wikipedia
yo
O si tun lo si Baptist Girls High School ni Ipinle Osun bakan naa..
wikipedia
yo
O gboye Bachelor's degree ni Obafemi Awolowo University to wa ni Ile-Ife ati Post-Graduate diploma ninu Journalism ni Nigeria Institute of Journalism to wa ni Ipinle Eko.Iṣẹ rẹFunke bẹrẹ iṣẹ to yan laayo gege bii Akowe ni Prime People Magazine..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ Punch Newspapers lọ́dún 1993 títí wọ 2000, nígbà tí wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi Amọyìko fún The Post Express on Saturday..
wikipedia
yo
Látìgbà náà ló ti jẹ́ àṣàtúnkọ́ fún ìwé-ìròyìn ThisDay àti Saturday Independent..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ asatunko fún ìwé-ìròyìn Sunday sun nígbà kan rí.Funke jẹ́ akọ̀ròyìn, olùdarí àti asatun agba fún Daily Telegraph Publishing Ltd.Ni ọdún 2006, United States Information Service (15] yàn án láti ṣiṣẹ́ lóri u.S..
wikipedia
yo
O jẹ okan lara awon omo egbe Federal Radio Corporation of Nigeria (FRCN).Funke egbemode to je Aare Nigeria Guild of Editors (ńgé) ni Commissioner for Information and Civil Orientation ni Ipinle Osun.Awon itọkasiàwọn omo YORÙ ara Naijiria..
wikipedia
yo
Dick Tiger (Orúkọ àbísọ Richard Ihetu; August 14, 1929 – December 14, 1971) jẹ́ ajẹ́ṣẹ́ tó gba World Middightight àti World Light Eèweight Championships..
wikipedia
yo
Tiger kó lọ sí Liverpool, ní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì láti lọ ṣiṣẹ́ ìjẹ́sẹ̀, at'ibẹ̀ ló ti kọ́ lọ sí Amẹ́ríkà.Wọ́n fi orúkọ Tiger sínú ilé olókìkí ìjẹ́sẹ̀ àgbáyé ní 1991..
wikipedia
yo
Ìwé-ìròyìn The Ring pèé ní Fiana of the Year (Ajése ọdún) ní 1962 àti 1965, bẹ́ẹ̀síní Boxing Writers Association of America (Ẹgbẹ́ Oniroyin Ijese Amẹ́ríkà) pee ni Fidu of the Year (Ajese Odun) ni 1962 ati 1966..
wikipedia
yo
Ní 2002, ìwé-ìròyìn The Ring ṣòbá fún Tiger ní ipò 31k bíi ajese olokiki jùlọ LÁGBÀÁYÉ.tiger jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Igbo, ó sì ja bíi àsọ fún Biafra nígbà ogun abẹ́lé Nàíjítọ́. Àwọn ajè ara Nàíjíríà..
wikipedia
yo
Katherine Esther Jackson (née Scruse, oruko àbísọ Kattie B..
wikipedia
yo
Ohun ni Iya Michael ati Janet Jackson ati awọn Ẹ̀gbọ́n Wọn.Ìtọ́kasíàwọn Ará Amẹrika..
wikipedia
yo
Joseph Walter Jackson (July 26, 1928 – June 27, 2018) jẹ́ mọ́níjà olórin ará Amẹ́ríkà àti Bàbá-Àgbà ìdílé Jackson, òhun ni Bàbá Michael àti Janet Jackson..
wikipedia
yo
Wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sínú ilẹ̀ àwọn olókìkí Rhythm and Blues ní 2014.Ìtọ́kasí ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O Adams (Ọjọ́ìbí May 4, 1953) jẹ́ akọrin ati Àtẹ ati Àtẹ Ara Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún agbára ohun rẹ̀.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Relola rẹ̀ ti wọ́n bí gẹ́gẹ́ bí Ajíhìnrere sí Ajíhìnrere, tí ó sì dàgbà sí gbígbọ́ Orin Ẹ̀mí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dàgbà, àwọn ẹbí rẹ̀ kòpọ̀ sì yapọ̀n, Washington..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ ní ṣọ́ọ̀ṣì.Kí ó tó rí ànfàní láti kọ orin rẹ̀, Adams fojú winá ọ̀pọ̀lọpọ̀ kíkọ̀sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1970s, ó kó lọ sí Los Angeles, California, níbi tí ó ti ó ṣe rẹ̀kò.Pẹ̀lú àmọ̀ràn olùkọ́ rẹ̀, lée Farrell, ó kó lọ sí Kansas City, Missouri, níbi tí ó ti ṣe àwọn oríṣiríṣi kíkọ orin ní ibi ìpéjọpọ̀.Ìgbésí ayé rẹni ọdún 1994, Adams fẹ́ onílù tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ John cusd ní Methodist Church tí ó wà ní Kansas..
wikipedia
yo
Wọ́n pàdé ní ọdún 1980 nígbà tí wọ́n jọ ń ṣe rẹ̀kòdù fún Adams.Awards and Nominationṣitọ́kasí akọrin ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Juan Martin del Potro Lucas () (ọjọ́ 23 September 1988), tàbí Delpo (), jẹ́ àgbà tí ara Argentina tó wà ní ipò No..
wikipedia
yo
122 lagbaye ni Tẹnis awon okunrin enikan Association of Tennis Professionals (ATP).Aṣeyọri Re to tóbi jùlọ ṣẹlẹ nigba to gba Ife-èye Open Amẹrika 2009 nigba to bori Rafael NDaldia ni semifinal ati Roger fèdè ni Final..
wikipedia
yo
Ohun ni eni akoko to bori fèdè ati naDalkun ninu idije Grand Rade kannáà ati ẹnìkan soso leyin awon ti a mo si Big Four (Roger fèdèï, Rafael NDaly, Novak dOyevic ati Andy Murray), to gba Ife-eye Grand Rale laarin Open Fránsì 2005 ati Open Amẹ́ríkà 2013..
wikipedia
yo
Ohun naa tun ni ara Argentina keji to gba Ife-eye Open Amẹ́ríkà nigba Open era.Ìtọ́kasí ayori Open Amẹrika..
wikipedia
yo
Bianca Vanessa andRees (; Ọjọ́ìbí June 16, 2000) ni agba Oroko ara Kánádà..
wikipedia
yo
4, Ohun ni ara Kánádà ti ipo re gajulọ lati ibẹrẹ ajo Women's Tennis Association (WTA)..
wikipedia
yo
AndRees gba ife-eye Open Amerika 2019 ati Ife-eye Open Kánádà 2019 nigba to bori Serena Williams ni ipari idije mejeeji.Ìtọ́kasí.Awon ayori Open Amẹrika..
wikipedia
yo
Sofia Anna Kenin (pẹ̀lú ìnagijẹ Sonya, ; Ọjọ́ìbí November 14, 1998) ni àgbà òiku ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ipò rẹ̀ tọ̀gájùlọ láàgbáyé àjọ Women's Tennis Association (WTA) ni No..
wikipedia
yo
Kẹ́nin gba Ife-eye Open Australi 2020 nigba to bori Gariney Muguruza ni ipari ìdùbúje naa, eyi so o di ọdọmọde kekere julọ ara Amẹrika to gba idije Grand Sale awon obinrin enikan leyin Serena Williams ni 2002.Ìtọ́kasí Ayori Open Australia..
wikipedia
yo
Jelena Oberenko (Ọjọ́ìbí 8 June 1997), Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi Alona Oodua, ní Àgbà Amẹ́ríkàs ará Latvia..
wikipedia
yo
5 Ninu awọn idije enikan to de be ni 19 March 2018, ati No..
wikipedia
yo
17 NÍNÚ ÀWỌN ÌDÍJE ẸNIYÀ, TÓ DÉ BẸ NÍ 2 March 2020..
wikipedia
yo
Openko gba ifẹ-eye Open Fránsì ọdún 2017 nígbà tó bori síMona Halẹ̀p ní Ìparí.Ìtọ́kasí Ayori Open Fránsì..
wikipedia
yo
Omijé jẹ́ omi kan tó mọ kànga tó.Ma ń sun jáde láti inú ibùsùn kan tó wà nínú ihò ojú.A lè ṣalábàápàdé omi yí ni ara gbogbo ẹranko afọ́nsannu tókù yàtọ̀ ewúrẹ́ àti ehorokoko iṣẹ́ omijéfìfo ìdọ̀tí inú ojú,ó ń jẹ kí ojú ó lè yí kiri pẹ̀lú ìrọ̀rùn,ó sì ń jẹ́ kí àwọn ọmọ ogun ara ó jí pépé sí.Ó má ń jáde látàrí ìmọ̀sí-lára tàbí bí ìṣẹ̀lẹ̀ bá ṣẹ̀ ṣe di ara..
wikipedia
yo