cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
TLC tun ni egbe akorin R&B akoko to gba iwe-ẹri ipawo million latọwọ ajo Cherayath Industry Association of Japan (riaj) fun FanMail (1999).Àwọn ẹgbẹ́ olórin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Usher Raymond IV (Ọjọ́ìbí October 14, 1978) ni akọrin, akọ̀wé-orin, òṣèré àti onijo ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí ní Dallas, Texas, ṣùgbọ́n ó dàgbà ní Chattanooga, Tennessee kò tó kó lọ sí Atlanta, Georgia.Ìtọ́kasí.Àwọn akọrin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Munachi Gail Teresa Abi Nwankwo jẹ́ olórin, akọrin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí tẹ́lẹ̀fíSi àti òṣèré ní ìpínlẹ̀ Nàìjíríà .. | wikipedia | yo |
Ó gbé igba ó ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó wàwá jùlọ ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ Ipinle Imo ni Naijiria.ibẹrẹpẹpẹ ati eto-ẹkọ rẹ rẹ wọn bii si Ile Port Harcourt, ibẹ̀ ni o si gbe dagba.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girl's College ni AbuPaulu.. | wikipedia | yo |
O lo si ile eko giga ti Benson Idahosa University nibi ti o ti ka International Relations and diplomacy.Iṣẹ o gbe igba o ròkè ninu idije obinrin ti o rewa julọ ni Naijiria ni ọdun 2007 ni igba ti o si wa ni Ile ẹkọ giga.. | wikipedia | yo |
Oun lo se asoju fun Naijiria ninu idije obinrin ti o rewa julo ni agbaye.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, òun àti ẹni tí ó gbé igba ó ròkè ní ọdún 2000 fún ìdíje obìnrin tí ó rewa jùlọ ní Nàìjíríà, Matilda Kerry jọ ṣiṣẹ́ pọ̀ láti sọ̀rọ̀ nípa àrùn jẹjẹrẹ.. | wikipedia | yo |
Munachi jẹ́ olórin, orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ ní Babyrélla kí ó tó padà wá yí sí múná.. | wikipedia | yo |
O ti kọ orin fun àwọn olorin bii J Martins ati wájẹ́.. | wikipedia | yo |
O si ma ṣe kopa ninu fiimu fun awọn olorin, o wa ninu fiimu EtoÀyà ti awọn p square ṣe.. | wikipedia | yo |
Ni osu kefa odun 2010, muna darapo mo ile ise ayo Shonaiya RDámásíkù company nibi ti o ti se awon orin re bii the goddess ati the hustler.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2011, múkàn darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Unilever níbi tí ó ti ṣe àwòṣe fún lux.. | wikipedia | yo |
ó ṣe atọ́kùn fún eré orí tẹ́lẹ́fíòn ti Malta Guinness Street dance Africa.Àwọn ìtọ́kasí àwọn akọrin ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Taiwo Ajai-cetttt (Bii ojo keta osu keji odun 1941) ni osere, oniroyin ati atọ́kùn ara ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Aja-Ilycett ni obinrin akọkọ ti o se ise olootu iwe-iroyin Africa Woman ní ọdún 1970.ibẹrẹseìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Lycett ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kejì ọdún 1941 ní ìpínlẹ̀ Èkó, bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìrán Awori.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Mt Carmel Convent School àti Methodist Girl's High School ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ó lọ sí ìlú London láti ka ìwé ìmọ̀ Business and Administration.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Hendon College of Technology níbẹ̀ ni ó ti gba HND nínú Business Studies ní ọdún 1969.. | wikipedia | yo |
ní ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, ó ń ṣiṣẹ́ ní kéde tea shop, ilé ìfìwé ránṣẹ́ àti ilé iṣẹ́ ìpolówó.Iṣẹ́ rẹ̀ó bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ sì ní ṣe eré ní ọdún 1966 ní gba tí ó kópa nínú eré The Lion and the Jewel.. | wikipedia | yo |
Kò lérò láti kópa nínu eré na tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n olùdarí eré náà, William Gaskill sọ fún pé kí ó wá kópa nínu eré náà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn eré náà ni ó wá lọ sí ilé ẹ̀kọ́ orin àti eré tí “Guild School of Music and Drama" * | wikipedia | yo |
Ó kópa nínú àwọn eré orí ìtàgé bíi Life Everlasting , the National Health àti Parel Post.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu àwọn eré ti Nàìjíríà bíi Tinsel àti Obiribiri.Ní ọdún 1975, Lycett darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ Africa Magazine.Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Society of Nigerian Theatre Artists (Sonta).Ẹ̀bùn àti ayẹyẹ ní ọjọ́ kìíní Oṣù Kẹwàá ọdún 2006, Lycett gba ẹ̀bùn Officer of the Order of Niger láti ọwọ́ Chief Olusegun Obasanjo.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kejì Ọdún 2008, wọ́n fi ṣe olórí British-African Theatre, pẹ̀lú dọ̀tun Adebayo àti Yemi Ajibade.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Nàìjíríààwọn oníròyìn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹtu ni a ún pe oríṣiríṣi àwọn ẹranko ajẹnu oníkà-didọ́gba tó jẹ́ àbínibí sí oríṣi agbègbè ní Afrika àti Eurasíà.Àwọn Arokobò.. | wikipedia | yo |
Irving Inperses rhames (ọjọ́ May 12, 1959) ní òṣèré tíátà àti fíú ará Amẹ́ríkà.àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ara Américo ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Kim Victoria Fields (ojoibi May 12, 1969) ní òṣèré àti olùdarí ètò tẹlifísàn ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Fields gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Dorothy "Tootie" Ramsey nínu eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣàn NBC The Facts of Life (1979-1988), àti gẹ̀gẹ̀ bíi Reoṣù Hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ Church Fox, Living Single (1993–1998–1998 | wikipedia | yo |
Fields ni ọmọ Chip Fields ti ohun naa jẹ oṣere ati oludari, ati Ẹ̀gbọ́n Alexis Fields.Àwọn itọkasi àwọn oṣere ara Ameria ọmọ Afrika Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Adaọ̀rá OnyeChere jẹ́ onílọ́n, oníṣòwò, ìwà àti òwé ní ilẹ̀ Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun si ni atọ́kùn ètò tẹ́lẹ̀ fún ètò Kakáàki, lórí Africa Independent Television.. | wikipedia | yo |
Òun sì ni atọ́kùn ètò Talk 2 Adaora lórí Kiss FM ní gbogbo ọjọ́ Ìṣẹ́gun ní Àgọ́ Mẹ́rin ìrọ̀lẹ́.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Women Eperìyá Women Everywher (wẹ́wẹ́).. | wikipedia | yo |
Oun naa ni oludari Adenature Heels Media.ibẹrẹ Aye ati eto-ẹkọ rẹ̀ wọ́n bíi sí ilẹ̀ Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ọmọ ìlú Okigwe ní Ìpínlẹ̀ ÌMỌ̀.. | wikipedia | yo |
Adaọ̀rá je akobi laarin awon omo mefa ti awon obi re bi.. | wikipedia | yo |
Adaora lọ si Ile Eko Starland Private School ni Ipinle Eko fun Eko ibeere.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Coventry University níbi tí ó ti ka ìwé ìmọ̀ òfin.. | wikipedia | yo |
O tun lọ si London Metropolitan University àti Oxford Brooks University.Iṣẹ ki o to pada si ilẹ̀ Nàìjíríà ni ọdun 2009, adaọ̀rá sise fun World View Magazine ni ile United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Adaora se agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun Coventry student radio ni igba ti o si je akekoo ni ile eko naa ki o to pada lo sise ni Channel 4 London.. | wikipedia | yo |
O sise fun ben Television ni London gege bii alátúnṣe ati olóòtú eto African Film Review.. | wikipedia | yo |
O sise agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun Confluré Cable Network limited ni Ipinle kogi, Federal Radio Corporation of Nigeria, Vision FM ati dáàr Communications.. | wikipedia | yo |
Ó dára pọ̀ Òsèlú ó si du oyè ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìpínlẹ̀ ìmọ̀ ṣùgbọ́n kò wọlé.. | wikipedia | yo |
Adaọ̀rá je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun eto Talk2Olaora lori Kiss 99.9 FM.. | wikipedia | yo |
Adaora je onkọwe, o si ti kọ awon iwe bii Poetry Poetry for Life, Black Girl with a White heart, Women in the World, Arise ati Fear.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹkẹ́ya (orúkọ àbísọ éíthne ní bhonain Ọjọ́ìbí May 17, 1961) jẹ́ olórin ọmọ ilẹ̀ Ireland.itokáì àwọn akọrin ará Ireland.. | wikipedia | yo |
Zainab Balogun (tí a bí ní ní ọjọ́ kẹwàá Oṣù Kẹwàá ọdún 1989) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó béèrè sì ní ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún.. | wikipedia | yo |
Ó wà nínú àwọn tí olùdásílẹ̀ the J-Iist TV, ní ibi tí wọ́n ti ma sọ̀rọ̀ nípa àṣà ilẹ̀ Áfríkà àti àwọn ọrọ̀ tí ó jọ mọ́.. | wikipedia | yo |
O sise agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun Ebony TV ni ibi ti o ti n se atọkun fun eto The Spot.. | wikipedia | yo |
O ti ṣe atọ́kùn ètò fún juMia TV naa.ibẹrẹṣe aye ati eto-ẹkọ rẹ wọ́n bíi Zainab si orilẹ-ede London, ṣugbọn awọn obi rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Sacred heart CC Secondary School .. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Kent ní ibi tí ó ti ka ìwé ìmọ̀ òfin.Balogun ṣiṣẹ́ fún Premier Models Management ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún gẹ́gẹ́ bi Modelíli.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin, ó kópa ninu àwọn eré bíi material girls, cocktail, the Charlatans ati The Dark Knight rises .. | wikipedia | yo |
Zainab jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún ilé iṣẹ́ EbonyLife TV ní ibi tí ó ti ń ṣe atọ́kùn fún wọn.. | wikipedia | yo |
O ti se atọkun fun eto bii el now, ati the spot.aye re ganganni osu karun-un odun 2018, Balogun fẹ Ọgbẹni dikko Nwachukwu, eyi ti o je oludasile TkonWest Airways.. | wikipedia | yo |
Àwọn méjì yìí ṣe ìgbéyàwó ìbílẹ̀ wọn ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Balógun máa ń dá àwọn àsìkò rẹ̀ láàrín London, England, àti Lagos, èyí tí ó jẹ́ ẹ̀kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ rẹ̀àwọn iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ tó ìtọ́kasí àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
ní àwọn ewéko tí eniyan tabi ẹranko mìíràn máa ń jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ.. | wikipedia | yo |
Ènìyàn lè ṣe ewébẹ̀ jẹ tàbí kí wọ́n jẹ ẹ́ ní tútù.. | wikipedia | yo |
Anfaani pọ̀ jantirẹrẹ nípa jíjẹ ewébẹ̀, pàápàá jù lọ ninu àgọ́-ara eniyan.. | wikipedia | yo |
Pupọ ninu àwọn ewébẹ̀ ló kún fún àwọn èròjà aṣaralóore bíi èròjà-ara afúnnilókun (carbohydrate), èròjà-ara amúnidàgbà (protein), ọ̀rá (fat) ati àwọn èròjà-ara amárajipẹpẹ (vitaminS).. | wikipedia | yo |
Oriṣiriṣi ewébẹ̀ ló wà, fún àpẹẹrẹ, ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀, ẹ̀fọ́ sóko, igbó, ewédú, ilá, gbúre àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, àwọn wọn máa ń ka àwọn èso jíjẹ mìíràn sí ewébẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọ̀gbìn.. | wikipedia | yo |
She Saad Al-Abdullah Al-Sasa Al-Sabah, Kcmg (Hon) ( SA'd AlTgainesibi Allah as-Salim as-sabah) (1930 – 13 May 2008) lo je emiri ile Kuwewe ati alase ologun ilẹ Kuwe fun igba sokí iye mẹsan (lati 15 dé 24 January 2006), nigba to ropo Sheikh Jaber.. | wikipedia | yo |
She Saad je oga alase ni ile-ise ologun ile Kuweiti, o tun je alakooo ile-ise akoso oro abele titi di February 16 1978.Since 1964.Ìtọ́kasí ara Kuwewe.. | wikipedia | yo |
William Manning Marable (May 13, 1950 – April 1, 2011) Ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Marable jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ètò ìgboro, ìtàn àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ní Yunifásítì Kobọ̀ùn.. | wikipedia | yo |
Marable ló jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé-ẹ̀kọ́ fún ìwádìí nínu àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
O ko iwe to po, o si kopa ninu akitiyan oselu RAWsiwaju.. | wikipedia | yo |
Àgbáǹréré ni ìkan ńnu irú-ẹ̀dá márùún oníkà-tokúpa ẹlẹ́sẹ̀ pátákó tó wà láyé nínú ìdílé irú-ẹ̀dá-àgbáǹréré (R8Cdae), àti àwọn irú-ẹ̀dá yíòwù tó jo won sùgbọ́n tí wón kò sí láyé mọ́.. | wikipedia | yo |
Meji ninu awon iru-eda to wa laye wa ni Afrika, meta si wa ni apaguusu Asia.Ìtọ́kasí eranko.. | wikipedia | yo |
Zain Yẹking Asher (Bii ni ọjọ ketadinlogbon osu kejo odun 1983) je omo orile ede Naijiria ati Britain, o je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun CNN International ni ile New York City.. | wikipedia | yo |
ó tún ma ṣiṣẹ́ fún money magazine.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọn bíi ní Balham, London borough of Wolùtọ́júworth, England, àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O si jẹ ọmọ ilu Ezeagu ni Ipinle Enugu ni ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2005 Ashley lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Keble College ní Oxford University níbi tí ó ti kọ́ èdè Spanish àti French.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Columbia University ní ibi tí ó ti kọ́ nípa ìmọ̀ ìròyìn.Iṣẹ́ ó darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ CNN ní Oṣù Kejì ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó darapọ̀ mọ́ CNN, ó ń ṣiṣẹ́ fún Money Magazine ní ibi tí ó ti kọ́ nípa ọ̀rọ̀ owó fún wọn.. | wikipedia | yo |
O ti sise fun New12 12 gege bi aláròyé lori telefíìsì.Awon Ìtọ́kasí awon araNaijiria Naijiria.. | wikipedia | yo |
Pearleña Igbokwe ni olori ní Universal Television èyí tí ó jẹ́ ẹ̀yà kan lára NBC Universal Television Group.. | wikipedia | yo |
oun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó wá láti Áfríkà tí ó ma ṣe olórí fún ilé iṣẹ́ tẹ́lẹ̀Fisinù ní orílẹ̀-èdè United States of America.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Ìgbò ní Nàìjíríà.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bíi Igbokwe ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní Nàìjíríà ní ìgbà 1960.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí orílẹ̀-èdè USA ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́fà.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti yalé University àti Columbia University.Iṣẹ́ Igbokwe bẹ́ẹ̀ rẹ̀ iṣẹ́ ìdárayá ní Showtime.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe adarí fún àwọn ère bíi nurse Jackie, the big C ati master of Sex.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2012, wọ́n fi igbokwe jẹ́ igbá kejì adarí fún ìdàgbàsókè ère ní NBC.. | wikipedia | yo |
O ṣe adari fun awọn ere bii the Blacklist, blindspot, Chicago Med, Shades of Blue, this is us, timeless ati taken.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, wọ́n fi jẹ́ alákòóso fún Universal Television, èyí tí ó fi jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ láti ilẹ̀ Áfríkà tí ó ma jẹ́ alákòóso fún ilé iṣẹ́ tẹ́lẹ̀Fisinu ní USA.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2018, Igbokwe dara pọ̀ mọ́ àwọn adarí fún HRts.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún náà ni ó dara pọ̀ mọ́ Napte.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ibi Alado Jamestown ni Ibi-àmúsìn Ilẹ̀ Virginia ló jẹ́ ibùgbé ibi ìtẹ̀dó àwọn gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ ní.Ìtọ́kasí-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
(Bọ́jọ́ibi May 14, 1944) ní AFIFIFI, ọlọ́rẹ, Aoti onísòwò ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Lucas gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tó ṣe àwọn fíú bíi Star Wars àti Indiana Jones, àti olùdásílẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ Lucasfilm, LucasaRTS ‘ati Indural Light & Magic.. | wikipedia | yo |
Ohun ni Alaga Lucasfilm tele ki o to taa fun The Walt Disney company ni 2012.Ìtọ́kasí oludari fíú ara Amerika.. | wikipedia | yo |
Rphael Ṣáàdìq (; Orúkọ àbísọ Charles Ray Wiggins; May 14, 1966) ni akọrin, akọ̀wé-orin, onílù-orin, àti olóòtú àwo-orin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ bii ọkan ninu ọmọ ẹgbẹ olorin Tony! Toñi! Tone! | wikipedia | yo |
O ti se olootu orin fun awon akorin miran bii joss stone, d'Angelo, TLC, en Vogue, kelis, Mary J.. | wikipedia | yo |
Bblige, lẹ̀dísi, Whitney Houston, Solange Knowles ati John legendÌtọ́kasí.Àwọn akọrin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Sandra pẹ̀lúluchukwu Ezekwesili jẹ́ oníròyìn àti Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni atọkun fun eto iroyin Drive Time ati eto Hard facts lori Nigeria Info 99.3 FM ni Ipinle Eko ni Naijiria.ibẹrẹṣe aye, eto-ẹkọ ati iṣẹ rẹ wọn bi si Ipinle Port Harcourt ni Naijiria, oun nikan ni obinrin laarin awọn ọmọ mẹta ti awon obi rẹ bi.. | wikipedia | yo |