cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O lọ si ile eko naowa Nursery and Primary School ni Enugu fun eko ibẹrẹ pepe rẹ..
wikipedia
yo
IṢẸ́ agbejọ́rò ni Sandra fẹ́ ṣe tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kò mú fún ìmọ̀ ẹ̀kọ́ òfin ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, kàkà bẹ́ẹ̀, ìmọ̀ ibi ìbánisọ̀rọ̀ ni wọ́n mú fún..
wikipedia
yo
Ni igba ti o wa ni ile eko giga, o lo si ile ise ti Enugu State Broadcasting Service (ESBS), nibe ni o ti ko ise agbóhùnsáfẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó ṣe tán ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Enugu State University of Science and Technology, ní bi tí ó ti ka ìwé ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀, ó ṣiṣẹ́ fún Sípéènì TV ní Nàìjíríà, lẹ́yìn tí ó kúrò ní bẹ, ó ti sí ṣe fún Radio Bàyél àti Ray Power FM ní yẹ̀nI..
wikipedia
yo
Ó bẹ́ẹ̀ rẹ̀ sì ni sì ṣe fún Cool FM ní oṣù kẹta ọdún 2013..
wikipedia
yo
Wọ́n fàá kalẹ̀ fún ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ obìnrin tó tayọ jùlọ ní ọdún 2014..
wikipedia
yo
Ó gba ẹ̀bùn láti ọwọ́ Stefano papatti Foundation ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Ni Oṣu kọkanla ọdun 2018, o kuro lati Cool FM si Nigeria Info 99.3 FM..
wikipedia
yo
Òun sì ni atọ́kùn ètò Hard facts tí wọ́n máa n ṣe ní ìrọ̀lẹ́ láti àgọ́ mẹ́ta di ago méje.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Yvonne glutamic-abasi Glory Ewere (Bii ni ojo keta osu keta odun 1987) ti oruko inagi re je YYẹct Vixen Ekwere je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati osere, oun si ni atọ́kùn eto e-Weekly lori Silver bird Television..
wikipedia
yo
O ti se atọkun eto lori Rypípẹ́ 93.7 FM naa.ibẹrẹṣe aye ati eto-ẹkọ rẹ Vixen je ọmọ Ipinle Akwa Ibom ni orile-ede Naijiria, oun si ni àbíkẹ́yìn ninu awọn ọmọ meje, ilu Eko si ni won bi si..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Air Force Primary School àti Holy Child College ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Lagos State University, ní ibi tí ó ti ka ìwé ìmọ̀ History and International Studies.DiOṣù/TV ó bẹ́ẹ̀ rẹ̀ sì ní ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ọdún 2008 ní ìgbà tí wọ́n fi ṣe atọ́kùn fún ètò Dance Part lórí Rhythm 93.7 FM..
wikipedia
yo
Wọ́n gbà gẹ́gẹ́ bíi olóòtú fún ẹ̀tọ́ ẹ-Weekly lórí Silver bird Television..
wikipedia
yo
O ti ṣe ifọrọwanilẹnuwo fun awọn gbajumọ eyan bii olori orilẹ-ede Naijiria tẹlẹ, Goodluck Jonathan, o si ti ṣe atọkun fun eto bii most beautiful girl in Nigeria 2012..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹwàá ọdún 2015, ó dá ètò tiẹ̀ sílẹ̀, ètò ná ń jẹ́ Drive Time with Vixen.films and Sosdáwọ́lé Yvonne tí kò pa nínú àwọn eré bíi 7 inch Curve, sin tó Caesar, Put a Ring on It àti gidi Up .ẹ̀bùnàwọn ìtọ́kasí àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Telechi Lawrence Nneeji (bíi ní ọjọ́ kọkàndinlógún osù kìíní ọdún 1987) ti oruko inagi rẹ̀ jẹ́ tóbẹ̃ dá diva jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti atọ́kùn ètò lórí tẹ́lẹ̀Fisinù..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, Thisday ni pé ètò rẹ̀ ní àwọn gbò jù ní Ọsàn ní apá ila-oorun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2013, o gbajumọ fun awọn ẹtọ bii Top Ten most ati the music commentators ti o ti ṣe atọkun fun ni Channel o..
wikipedia
yo
O ṣe aṣoju fun Naijiria ni bet's Top Actor Africa ti won se ni igba keji..
wikipedia
yo
Ó ní ètò kan tí ó ń ṣe tí ó fi wá àwọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀.Ìbẹ̀ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ òun ní àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí..
wikipedia
yo
O lọ si ile eko giga ti MaDonna University ni bẹ si ni o ti gboye Economics ni ọdun 2007..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju si ile eko University fun Masters degree re ninu Economics.Iṣẹ ni ojo karun-un lélógún, Oṣu kejila ọdun 2007, ni o kọkọ se agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun Vision FM ni Abuja..
wikipedia
yo
O lo si Kiss FM ni ọdun 2009, o si di olori awon agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni odun 2011..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2012, o lo dara po mo nse FM ni Enugu, o si di adari eto nibẹ..
wikipedia
yo
Tobechi ti si ṣe pẹlu awọn ile iṣẹ bii Gulder, Amstel Malta, Nokia ati Airtel gẹ́gẹ́ bi olóòtú fún àwọn ẹ̀tọ́ wọn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó wà láàarín àwọn ó lu díje ní MTV Base Vtra Search..
wikipedia
yo
Ni odun ti o te le, o ko pa ninu idije The Next títan TV Show, o si gbe ipo kẹfa..
wikipedia
yo
Tobechi jẹ ikan laarin awọn oṣere ninu bet's Top Actor Africa, eyi si ni igba akoko ti o ma se ere..
wikipedia
yo
ní ọdún 2017, kĩ ṣe eré ìwé ìtàn fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí, ó sì pe àkọlé rẹ̀ ní The 4th Decade..
wikipedia
yo
O da eto MPW Podcast series ati the Anaweters vlog kalẹ̀ láti lè pèsè ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí o bá fẹ́ ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́.ẹ̀bùnàwọn Ìtọ́kasí Nigerian Radio personarezhou University (HHhi) Aludọ́gba of Calabar alumniawọn Eniyan AAlààyèta Television Talk Show Hoobasígbó Radio personali|u Television personarezhou from Imo (Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1986's College, Lagos alumni..
wikipedia
yo
Nnenna Egwúmìíràn: (Bii ni ọjọ keji lelogun oṣu Kẹsán-an ọdun 1992) ti oruko inagi re je nenny B je omo Naijiria, o si je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fun MTV Base Africa.ibẹrẹ aye ati eto-ẹkọ rẹ won bi Nnenna si Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ àlòysius Primary School ní Abuja fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
O lo si ile eko giga ti ChukwuEmeka Odumegwu Ojukwu University ni ibi ti o ti gboye ninu eko ede geesi ati Mass Communication..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní University of Wollongong.Iṣẹ́ ó béèrè iṣẹ́ ní ọdún 2007 ni 2007 Kora Awards ní ìgbà tí ó gbé 50 cent..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, ó sì ṣe pẹ̀lú Africa Independent Television, AIT, gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ ṣe nínú ètò Matter Arising ..
wikipedia
yo
O kò pa nínú ètò X-Lefactor West Africa àti Star The Chete iṣ ní ọdún 2014..
wikipedia
yo
O darapọ mọ News Agency of Nigeria (NAN) Gẹgẹ bíi Oniroyin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó darapọ̀ mọ́ Hot 98.3 FM gẹ́gẹ́ bi atọ́kùn fún ètò Daily Drive Time Show àti Battle of the Sexes..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2017, Radio Magazine fi Nenny b sí ojúewé àkọ́kọ́ wọn, wọ́n sì pè ní ìkan láàrín àwọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó tayọ jùlọ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti se atọkun fun awọn eto bii my Big Nigerian Wedding, La Belle Africa, Trace afrobeat show, Johnnie Walker Jazz & whiskey night, AMVCA after Party, JamRock, Celeb Living..
wikipedia
yo
Ni Oṣu kọkanla ọdun 2017, ni Ile iṣẹ nkataa fi ṣe aṣojú fún wọn..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2018 ni ó tí n sì ṣe fún MTV Base Africa gẹ́gẹ́ bi V.ẹ̀bùnàwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1992People From Imo StataLọ́dún Television Anadters, Radio Predsígbó Television personalities, Radio personalities Talk Talk Show Hosígbó Radio personalities..
wikipedia
yo
Laura Monyeazo abẹ̀bẹ̀ (bíi ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1989) tí orúkọ ìnági rẹ̀ jẹ mọ́et abẹ̀bẹ̀, jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti òṣèré ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó béèrè sí ní di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó dáwá sí ní ṣíṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún Soundcity TV..
wikipedia
yo
Ó ń ma ṣe atọ́kùn fún ètò one on one show, body & Soul àti global Countdown show ..
wikipedia
yo
Ní gba tí ó wà ní Soundcity, ó kópa nínu àwọn eré bíi Red Card, Oasis àti Living kẹnu..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó dáwá sí ní ṣe atọ́kùn fún ètò The takeover" ní orí Soundcity Radio 95.8..
wikipedia
yo
O da ile ise ti won ti ta onje kale pelu iya re, oruko ile ise naa ni LL Occasiìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ aye ati eto-ẹkọ rẹ won bii Laura si orile ede United Kingdom, o si lọ si ile eko Corona Ikoyi Primary School nibi ti o ti se eko ibere pepe re..
wikipedia
yo
O lo si Ile Eko Dwen College fun odun kan, ki o to wa lo si Woldingham school ati St..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Manchester níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ òfin.Iṣẹ́ & Radio Presenter ó sì ṣe pẹ̀lú Soundcity TV àti Soundcity Radio..
wikipedia
yo
Ó sí ti gba àwọn gbajúmọ̀ olórin bíi Vector (Jóṣúà), 2baba, Olamide, Chidinma àti D'Banj lórí ètò rẹ̀.òṣèré ó ti kó pa nínú àwọn eré bíi Red Card, Oasis àti Living Onicement.Ẹ̀bùn Laura gba ẹbuǹ PERMEIA of the Month lati ọwọ́ Meets Media, wọ́n sì pèé fún ẹmọ̀ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Ori tẹ́lẹ̀ tó tayọ jùlọ lati ní owó òqute Magazine. 2 Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1989àwọn ènìyàn òEducation in Manchester in Manchester in Manchester of the University of Manchester National MeOnídàájọ́..
wikipedia
yo
Mary UDuma (Bii ni ojo mẹẹdọgbọn osu karun-un odun 1952) je oludari ni e meji fun Nigeria Internet Regiaver Association (nira)..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga fun Nigeria Internet Governance Forum.Eko Udoma gboye ninu Eko Accounting lati Ile Eko giga ti Institute of Management Technology ati University of Lagos.Iṣẹ UDuma Si ṣe pẹlu Federal AuÒdodo ni igba ti o wa ni Ile ẹkọ giga ti University of Lagos..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1995, ó darapọ̀ mọ́ Nigerian Communications Commission gẹ́gẹ́ igbá kejì adarí ọ̀wọ́..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1999, ó di ìgbà kejì adarí ní ẹ̀ka ti tariff and Charges..
wikipedia
yo
Wọ́n gbe lọ sí Corporate Planning ní ọdún 2005, ó sì ṣiṣẹ́ níbẹ̀ fún ọdún kan kí ó tó di adarí fún liCensing..
wikipedia
yo
Ó di olórí fún ẹ̀ka wómúwómúmers Affairs ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
UDuma ti se igba keji oludari fun Nigeria Internet Regiaver Association ki o to wa di oludari keji fun ẹgbẹ naa..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga fun Nigeria Internet Governance Forum..
wikipedia
yo
O se asoju fun GG ni odun 2019 ni ayeye ojo ti won ya kale fun awon obinrin ni gbogbo agbaye ti won se ni Abuja.ebun ni odun 2016, o gba ebun lati odo nira Presidential Award.Awon itọkasi awon eniyan alààyẹ̀1952 birthbóyáversity of Lagos alumníní women, Business executives..
wikipedia
yo
Ìtùnú Enthnu (bíi ní ọjọ́ kejì dínlógún oṣù kìíní ọdún 1959) jẹ́ ọmọ ogun orí omi Nàìjíríà àti ayàwòrán fún ìkọ́lé..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí ó ma jẹ́ ọmọ ogun orí omi, ó sì wà láàrín àwọn ayàwòrán àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ ológun orí omi ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní oṣù kejìlá ọdún 2012, ó di obìnrin àkọ́kọ́ ní Afrika tí ó ma di alábòójútó ẹgbẹ́ ológun orí omi.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí itùnú ní ọjọ́ kejì díndínlógún oṣù kìíní ọdún 1959..
wikipedia
yo
O lo si ile eko giga ti University of Nigeria nibi ti o ti gboye ayaworan fun ikole.Iṣẹ Iìtùnú je obinrin akọkọ ti o ma darapọ mọ National defence Academy ni Abuja ni ọdun 1985 oun si akekoo to tayo julo láàarín awon e legbe re..
wikipedia
yo
Ìtùnú ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó o MA ṣe olùkọ́ ni Armed forces Command and Staff College ní Jaji..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó ń kọ́ àwọn obìnrin ológun ní orílẹ̀ ède Libelé..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kejìlá, wón fi se alábòójútó ẹgbẹ́ orí omi ní Nàìjíríà, èyí ló fi jẹ́ kí ó jé obìnrin àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Áfríkà tí ó ma dé ipò náà.Àwọn ìtọ́kasí 1959 Birthsáwọn ènìyàn Alààyèta Navy Adlsls AdlslsNigerian Women FfNigerian Female Military perṣọnne of Nigeria, Nsukka, Nsukka Alug defence Academy Alumọ̀gád Women's History..
wikipedia
yo
Margaret Ogunàh ti oruko inagi rẹ jẹ Erelu je Ẹngi ati oludari fun Bamsat Nigeria Limited..
wikipedia
yo
Oun ti se igba keji adari fun Nigerian society of gègéỌpẹ́Ìdílé (nse), Olùkede fun Association of Professional Bodies of Nigeria..
wikipedia
yo
O ti ṣe alaga fun Nigeria Society of Gekemónì ni ẹya ti Ikeja.Iṣẹ o gboye gege bi Ẹngi oni kẹ́míkà ni odun 1986..
wikipedia
yo
O dara po mo ẹgbẹ Nigeria Society of GyàráÌdílé ni ọdun 1995..
wikipedia
yo
O di igba keji adari fun Nigerian Society of Pámónì ni ọjọ keje oṣu kọkanla ọdun 2014...
wikipedia
yo
Ni ojo keedogun osu kesan-an odun 2017, ni won fi si inu Nigeria's Construction Industry Hall of Fame..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, Margaret ṣe aṣojú fún ńṣe ní Sierra Leone, tí ó sì sọ̀rọ̀ nípa kókó ìwúlò lílo àwọn èyàn tí ó tọ́ ní ilé iṣẹ́..
wikipedia
yo
Ó sọ ọ̀rọ̀ nipa ti àìtó òun èlò amáyédẹrùn ṣe n dẹ́kun igaba orilẹ̀ èdè Nàíjíríà ni Àkúrẹ́ nibi ètò ti àwọn nṣe gbé kalẹ̀..
wikipedia
yo
O wa laarin awon ti o se ifọwọsi awọn ile ẹkọ giga ni ọdun 2018..
wikipedia
yo
O gba ẹbun Idanimọ pataki lati ọdọ Nigeria Society of PaNiger ti ẹya Ikeja ni ọdun 2017.Awon itọkasi awọn eniyan Alààyè Chemil Gwẹ́wẹ́Ìdílé Chief Abtives-
wikipedia
yo
Láti Masha jẹ́ adarí fún Olx àti Olorì òwò fún Google ní Nàíjíríà..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ babban Gonatẹ́nì Farmers Service Limited.ẹkọ lọ́lá gboyè Ẹngi láti ilé ẹ̀kọ́ gíga ti University of Virginia..
wikipedia
yo
O gba PhD ninu Eko Ẹngi lati ọwọ́ UC Berkeley College of Engineering.Iṣẹ Masha ni oludari fun Olx ni Naijiria..
wikipedia
yo
O se aṣoju fun Olx lati gba ebun Classified Advert website of the Year lati owo béàcon ICT..
wikipedia
yo
O sise fun McKinsey & company ni odun 2007 gege bii onimoran..
wikipedia
yo
Ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bíi olórí ìdàgbàsókè owó fún Google fún ọdún mẹ́rin..
wikipedia
yo
Ni ayẹyẹ ọdún karùn-ún ti Olx, lọ́lá gba ìjọba ní ìyanjú pé ki wọ́n ṣe àwọn ọna ìníṣe tí ó pé fún àwọn ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Lọlá wà láàrín àwọn olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ babban Goname Farmers Service Limited.Awon Ìtọ́kasí UC Berkeley College of Engineering AlutheUniversity of Virginia School of Engineering and Applied Science AluhanWomen Chief Execupt Eniyan AAlààyè Women..
wikipedia
yo
Aisha Augie-Kuta (ti a bi ni ọjọ́ kẹrinla oṣù kẹrin ọdún 1980) jẹ́ olùyàwòrán àti òṣèré fíìmù ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó dá ní ìlú Àbújá ..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ni Hausa lati ijọba ibilẹ Argungu ni Ariwa Nigeria..
wikipedia
yo
ó gba ẹ̀bùn náà fún olùṣọ́ọ́ko Ẹlẹda ti ọdún ní ọdún 2011 The Future Awards . ..
wikipedia
yo
Augie-Kuta ni Onimọnran Pataki ti isiyi (Ọgbọn Awọn ibaraẹnisọrọ oni nọmba) si Minisita fun Iṣuna-owo ati Eto Ilu..
wikipedia
yo
Ṣaaju si eyi o jẹ oluranlowo pataki pataki fun Gomina ti Ipinle Kebbi, Nigeria lori Media Titun..
wikipedia
yo
Augie-Kuta ṣe itọsọna ọpọlọpọ awọn ipilẹ idagbasoke fun agbawi ti ọdọ ati ifiagbara fun awọn obinrin kaakiri Nigeria.ìgbésíayé a bi Aisha Adamu Augie ni Zaria, Ipinle Kaduna, Nigeria, Augie-Kuta jẹ ọmọbinrin Oloogbe Senator Adamu Baba Augie (oloselu / olugbohunsafefe), ati Onidajọ Amina Augie (JSC)..
wikipedia
yo
Augie-Kuta bẹrẹ si ni nifẹ si fọtoyiya nigbati baba rẹ fun u ni Iitan ni ọdọAugie-Kuta gba oye oye ni Mass Communication lati Ile- ẹkọ giga Ahmadu Bello, Zaria ati pe o n kawe fun MSc ni media ati ibaraẹnisọrọ ni Pan African University, Lagos..
wikipedia
yo
Augie-Kuta ni awọn iwe-ẹri ninu ṣiṣe fiimu oni-nọmba lati ile- ẹkọ giga fiimu tuntun ti New York ati títọ́jú awọn ifihan aworan àsikò lati ọdọ Chelsea College of Arts, London, UK..
wikipedia
yo
Augie-Kuta di alabaṣepọ fun Nigeria Leadership Initiative (NAM) ni Oṣu Karun ọdun 2011..
wikipedia
yo
O tun jẹ Igbakeji Aare ti Awọn Obirin oni Fiimu ati Telifisonu ni Nigeria, ipin ti Iwọ-oorun Afirika ti nẹtiwọọki ti o da lori Amẹrika..
wikipedia
yo
O se agbekale photowagon, apapo fọtoyiya ti Naijiria, ni ọdun 2009..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2010, Augie-Kuta wa, pẹlu awọn obinrin Naijiria aadọta miiran, ninu iwe kan ati oníbodè fun awọn ayẹyẹ 50 @ 50 ti Orilẹ-ede ti o ni atilẹyin nipasẹ Awọn Obirin fun Change Initiative..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2014, Augie-Kuta ṣe iṣafihan fọtoyiya adashe akọkọ rẹ, ti a pe ni Alternate Evil ..
wikipedia
yo
O ti ṣe àwọn ìfúnni sí ìdàgbàsókè ọmọdébìnrin / Ìdàgbàsókè ọmọdé àti kíkọ́ orílẹ̀-èdè..
wikipedia
yo