cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ẹ̀wẹ̀, ìnáwó ní ọ̀nà tàbí ìwà wa lórí bí a ṣe ń náwó..
wikipedia
yo
Ohun pataki ni láti ṣetoo bí a óo ṣe máa ná àwọn owó tó bá wọlé fún wa..
wikipedia
yo
Ní àkókò ná, èyí yóò jẹ́ kí a mọ ìṣírò oye owó tó ń wọlé fún wa yálà lọ́sẹ̀ ni ó tàbí lóṣù, bí ó sì ṣe lọ́dún gan-an ni..
wikipedia
yo
Bákan náà, yóo tún mú kó rọrùn fún wa láti mọ àwọn ọ̀nà tí owó náà ń bá lọ..
wikipedia
yo
Síwájú síi, ẹ̀tọ́ yóò ràn wá lọ́wọ́ láti le ní ìkóra-ẹni-níjàánu lórí bí a ṣe ń nawọ́ wa..
wikipedia
yo
Bí a bá ti mú ìṣàkòtún tán, tí a tún mú ìṣàKosi náà, isàkùsà ni yóo kú nílẹ̀..
wikipedia
yo
Tí a bá yó ti ẹ̀tọ́ kúrò nínú ojúṣe ìjọba pàápàá sí ará ìlú, èrè ọmọdé ni ìyókù yóò jẹ́..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ẹ̀ka ìjọba pátá-porongodo ló máa ń ní àgbékalẹ̀ ìlànà tí wọn yóo tẹ̀lé láti mọ òye owó tí wọn ń retí ati èyí tí wọn óo ná bóyá fún odidi ọdún kan ni o tabi fún oṣù díẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí ni wọ́n ń pè ní ‘Ètò ìṣúná’ Ìdí nìyí tó fi ṣe pàtàkì fún gbogbo tólórí-Telemu, Tonga-ton kí kúlúkú ní ètò kan gbòógì lọ́nà bí yóò ṣe máa náwó rẹ̀..
wikipedia
yo
Yorùbá bọ̀ wọ́n ni, “Eku tó bá ti ni ọ̀pọ̀ nílẹ̀, kì í sì aré sá..
wikipedia
yo
Bí a bá ti ṣe àlàkalẹ̀ bí a óò ṣe nawọ́ wa yóò dín inákùùná kù láwùjọ wa..
wikipedia
yo
Ìnáwó abàádi pàápàá yóò sì máa gbénú ìgbé wọ́ wa láwùjọ wa..
wikipedia
yo
Mo ti sọ lẹ́ẹ̀ẹ̀kan nípa àwọn ẹ̀ka ìjọba mẹtẹẹta orílẹ̀ èdè yìí tí wọ́n máa ń ṣètò ìnáwó wọn..
wikipedia
yo
Àwọn wo ló tún yẹ kó máa ṣètò ìnáwó? Àwọn náà ni àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, àwọn oníṣòwò, àwọn ọmọ ilé-ìwé, níbi àṣeyẹ..
wikipedia
yo
Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba gbọdọ̀ ṣètò ìnáwó wọn kò sì gún régé..
wikipedia
yo
Ẹni tó ń gba ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá naira lóṣù tí kò sì fi òdiwọ̀n sí ìnáwó rẹ̀ Nípa títò wọn lẹ́sẹẹsẹ lè máà rówó sóhun tó yẹ làáakọ tó yẹ nígbà tí ó bá ti nawọ́ rẹ̀ sí àwọn ohun mìíràn tó ṣeéṣe kò nítumọ̀ ṣùgbọ́n tí kì í ṣe fún àkókò náà..
wikipedia
yo
Irú wọn á wá má rahan owó tóṣù bá ti dá sí meji tabi kí wọ́n jẹ gbèsè dé owó oṣù mìíràn..
wikipedia
yo
Síwájú sí i, àwọn oníṣòwò gbọdọ̀ máa ṣètò tó jíire lórí ìnáwó wọn..
wikipedia
yo
Nípa ṣíṣe èyí, wọn óo ní anfaani láti mọ̀ bóyá alaafia ni iṣẹ́ wọn tabi ọlanrẹ̀yìn..
wikipedia
yo
Níbi tí àtúnṣe bá sì ti pọn dandan, “A kì í fọ́dú ọ̀yà sùn ká tó í nà án ládàá,” wọn kò ní í bẹ́ṣú bẹ̀gbà, wọn óo sì ṣe àtúnṣe ní wéréwéré..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ ilé-ìwé gan-an gbọdọ̀ mọ̀ pé ká ṣètò ìnáwó ẹni kì í ṣohun tó burúkú bí ti í wù kó mọ..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi ọmọ ilé ẹ̀kọ́ giga, béèyàn bá gbowó fún àwọn oriṣiriṣi ìnáwó lati ilé lórí ẹ̀kọ́ ẹni, ó ṣeéṣe kí irú ẹni bẹ́ẹ̀ máa ná ìná-àpà tó bá dé ààrin àwọn ẹlẹgbẹ́ẹ rẹ̀..
wikipedia
yo
Irú wọn ló máa ń pe ọ̀sẹ̀ tí wọ́n bá ti ilé lọ́dọ̀ àwọn òbí wọn dé ní ‘ọ̀sẹ̀ Ìgbéraga’ èyí kò yẹ ọmọlúàbí páàpáà..
wikipedia
yo
Ṣíṣe ètò tó gúnmọ́ lórí ọ̀nà tí à ń gbà nawọ́ kò pín sí àwọn ọ̀nà tí mo ṣàlàyé rẹ̀ sókè yìí..
wikipedia
yo
Mo fẹ́ kó yé wa pé a lè ṣètò ináwó wa níbi àwọn ohunn ayẹyẹ bí ìsọmọlórúkọ [tàbí ìkómọjáde], igbeyawo, òye jíjẹ, ìṣìlè, àti ìsìnkú àgbà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Yóo ràn wá lọ́wọ́ láti fi bí a ṣe tọ́ hàn wá ká lè mọ ohun tí a óo dágbá lé níbi irúfẹ́ àṣeyẹ tí a bá fẹ́ í ṣe..
wikipedia
yo
Nípa bẹ́ẹ̀ a ò ní í sí ninu àwọn tó máa ń pa òwe tó máa ń mú kí wọ́n kábàámọ̀ nígbẹ̀yìn ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Òwe wọn ni, “Rán aṣọ rẹ bí o bá ṣe ga mọ́.” Èyí tí wọn ì bá fi wí pé “Rán aṣọ rẹ bí o bá ṣe lọ́wọ́ọ rẹ̀ sí.” Bí ẹni tó ga bá rán aṣọ rẹ̀ ní ‘Fò’ bó ṣe lọ́wọ́ mo ni, kò sì fẹ́ í ṣàṣejù..
wikipedia
yo
Irú ẹni bẹ́ẹ̀ lẹ ti mọ̀ pé aláṣejù péré ní í tẹ̀..
wikipedia
yo
Bí a bá wá fẹ́ láti ṣètò ìnáwó wa, ó yẹ ká mọ̀ pé itọ́ lọ lÓyọ̀ọ́, oníbodè lọ láààfin, ẹnìkan kì í fi kẹ̀kẹ́ ṣíwájú ẹṣin..
wikipedia
yo
Ìnáwó tó bá ṣe kókó jùlọ tó sì ń béèrè fún ìdásí ní kíákíá ló yẹ ká fi síwájú bí a ṣe ń tò ó ní ẹsẹẹsẹ..
wikipedia
yo
Eto ọrọ ajeọrọ ajeAjíbọ́lá, Olaniyi Ọlábọ̀dé Olaniyi Ọlábọ̀déeto Ọrọ̀ AjéYorùbá to won ni ki la o jẹ lágbà ki la o se, abalajo ti eto aje fi múmú láyà lóríggo Orílẹ̀ Èdè Àgbáyé toô bẹ̀..
wikipedia
yo
Gbàrà tí ọ̀nà káràkátà oní-pa sì pààrọ̀ tayé ọjọ́ tún ti dọ̀tun ìgbàgbé ni ètò ajé ti dọ̀tun tó gbòòrò síwájú sí..
wikipedia
yo
Àwọn eniyan wàá bẹ̀rẹ̀ síí ní lo àwọn ohun èlò bíi wúrà ati jákajì láti máa fií ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn ohun tí wọ́n nílò..
wikipedia
yo
Eléyìí mú kí káràkátà láàrín-in ìlú àti orílẹ̀ èdè tún gbìnàyá síi nígbà tí àwọn kù díẹ̀ kù díẹ̀ tí ń fa ìdílọ́wọ́ nínú káràkátà onípàṣípàrọ̀ ti kúrò ní bẹ̀..
wikipedia
yo
tí àbá kọ́kọ́ gbé ètò ayé ní orílẹ̀ èdè aláwọ̀ dúdú yẹ̀ wò fínní fínní, aoríi pe ohun ère oko ló jẹ́ lájorí ọrọ̀ ajé àwọn ènìyàn yìí..
wikipedia
yo
Àwọn ère oko wọ̀nyí ni wọ́n sì ń fi ń ṣe pàṣípàrọ̀ láti tan àìní ara wọn ṣáájú alábàápabé wọn pẹ̀lú àwọn aláwọ̀ funfun..
wikipedia
yo
Kéré kéré, ìlànà àti máa lo ọwọ́ wa sí ojútáyé, tí ètò ọrọ̀ ajé sì wá búrẹ́kẹ́..
wikipedia
yo
Ṣugbọn pẹlu ìbúrẹ́kẹ́ ọrọ̀ ajé yìí, ìyípadà díẹ̀ ló dé bá ipò ó sì ti àwọn aláwọ̀ dúdú yìí ti wà tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀rí..
wikipedia
yo
Eyi tó pọ̀jù ninú èrè ọrọ̀ ayé igbà ló dé yio lonlo si ọ̀dọ̀ àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun..
wikipedia
yo
Kàyéfì ńlá ló jẹ́ pé bí ọ̀rọ̀ àwọn aláwọ̀ funfun yìí ti ń pọ̀ sin í òṣì túbọ̀ ń bá àwọn aláwọ̀ dúdú fínra sí..
wikipedia
yo
Kàyéfì ọ̀rọ̀ yìí ò ṣẹ̀yìn ìwà ìmúni sin àdáni lọ̀rọ̀ tí àwọn aláwọ̀ funfun yìí fimú àwọn gìrìpá tó yẹ kó fi gbogbo ọpọlọ àti agbára wọn ṣiṣẹ́ láti mú ayé ìrọ̀rùn wàá bá ilé wọn àti àwọn ènìyàn wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tó yẹ kí àwọn gìrìpá aláwọ̀ dúdú máa ṣiṣẹ́ ìdàgbàsókè ní ìlú ìbílẹ̀ wọn, ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ funfun ni wọ́n wà tí wọ́n ń bá àwọn ènìyàn yìí ṣiṣẹ́ àṣekúdórógbó..
wikipedia
yo
Awon alawo funfun yii nlo awon alawo dudu lati tun orile ede ti won se, ati lati pilẹ̀ oro aje to laami laka..
wikipedia
yo
Gbogbo ìgbà tí ìmúni lẹ́rù yìí ń lọ lọ́wọ́, tí ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ funfun yìí sì ń tẹ̀ síwájú, kò sí ẹyọ iṣẹ́ ìdàgbàsókè kan ní orílẹ̀ èdè aláwọ̀ dúdú..
wikipedia
yo
Ìgbà tí òǹṣèwélẹ́rù dáwọ́ dúró, lẹ́yìn ìgbà tí àwọn aláwọ̀ funfun yìí ti gòkè àgbà díẹ̀ ń ṣe ni wọ́n tún yára gba ètò ìṣàkóso ìjọba lọ́wọ́ àwọn aláwọ̀ dúdú, tí wọ́n sì sọ pé, ọ̀làjú ni àwọn fẹ́ẹ́ fi wo àwọn aláwọ̀ dúdú yìí tí ẹ̀wù ìdí nìyí tí àwọn fi tẹ̀ wọ́n lôríba tí àwọn sì fi pa gba ìjọba wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n wá fi ti pa ti kùùkú sọ ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú di oko ọ̀gbìn àwọn ohun èlò tí wọn ń lò tí àwọn ilé iṣẹ́ ńláńlá tí wọ́n..
wikipedia
yo
Ipò ìṣe àti ìmúni sìn yìí ni àwọn aláwọ̀ dúdú wà tí ti fi di ìgbà tí wọ́n sọ pé àwọn funfun wọn ní òmìnira..
wikipedia
yo
Ipò òṣì àti àré tí àwọn aláwọ̀ funfun fi àwọn ènìyàn yìí sí kò jẹ́ kí wọ́n ó lè dá dúró, kí wọ́n sì dángbajíà láti máagé àwọn ohun tí wọ́n nílò ní ilé iṣẹ́ ìgbàlódé tí wọ́n fún ràá wọ́n..
wikipedia
yo
Àwọn aláwọ̀ funfun yìí ló sì wá ń dá iye owó tí ohun eré oko tó ń wá láti ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú yio jẹ́, èyí tí ó ń túmọ̀ sí pé, ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun yìí ní dídó lọ̀rọ̀ àti òdìkejì àwọn ènìyàn aláwọ̀ dúdú wà..
wikipedia
yo
Ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun yìí ni ètò ọrọ̀ ajé àgbáyé wà, tó bá sì ṣe wun wọn ni wọ́n ń lò ó..
wikipedia
yo
Abalajọ́ tó fi jẹ́ owó tí wọ́n ń ná nílùú wọn fínṣe ìdíwọ̀n pàṣípàrọ̀ ọjà ní Ọjà Àgbáyé..
wikipedia
yo
Kódà, àwọn orílẹ̀ èdè kan tó ní àwọn ohun àmúṣọrọ̀ kan tí àwọn aláwọ̀ funfun yìí ò fi bẹ́ẹ̀ ni, bíi epo rọ̀bì ò he è dá ohun kan ṣe lórí ohun àmúṣọrọ̀wọn yìí láì sí ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun yìí níbẹ̀..
wikipedia
yo
Abalajọ́ tó fi ṣòro láti rí orílẹ̀ èdè aláwọ̀ dúdú kankan nínú àwọn orílẹ̀ èdè tó ti gòkè àgbà..
wikipedia
yo
Ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun ni agbára ètò ọrọ̀ ajé àgbéye wà, àwọn ló sì n pàṣẹ fún àwọn orílẹ̀ èdè tó kù ní pa ọ̀nà tí wọn yíò gbà ṣe ìjọba àti ọ̀nà tí wọn yíò gbé ọrọ̀ ajé wọn gbà, tí wọ́n bá fẹ́ àjọ sepo dídán mọ̀ràn pẹ̀lú àwọn...
wikipedia
yo
ìṣèlú tàbí òṣèlú ni ìgbésẹ̀ bí àwọn ìdìpọ̀ ènìyàn kan ṣe ń ṣèpinnu..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ yí jẹ́ mímúlọ sí ìwúwá nínú àwọn ìjọba abẹ́lẹ̀.ìṣèlú nílẹ̀ Yorùbá ní àwùjọ Yorùbá, a ní àwọn ọ̀nà ìṣèlú tiwa tí ó dá wa yàtọ̀ sí ẹ̀yà tàbí ìran mìíràn..
wikipedia
yo
Kí àwọn òyìnbó tó dé ni àwa Yorùbá ti ní ètò ìṣèlú tiwa tí ó fẹsẹ̀múlẹ̀..
wikipedia
yo
Yàtò sí tí àwọn ẹ̀yà bí i tí Ìgbò tí ó jé wí pé àjọn ni wọ́n ń fi ìjọba tiwọn ṣe (Acephawáyé) tàbí ti Hausa nibi tí àṣẹ pípa wà lọ́wọ́ ẹnìkan (centra)..
wikipedia
yo
Èyí sì fi ipa tí àwọn òbí n kó nínú ilé ṣe ipilẹ̀ ètò òṣèlú wá..
wikipedia
yo
BÀBÁ TÍ Ó JẸ́ OLÓRÍ ILÉ NI Ó JẸ́ olùdarí àkọ́kọ́ nínú ètò ìṣèlú wá..
wikipedia
yo
Gbogbo ẹ̀kọ́ tó yẹ fún ọmọ láti inú ilẹ̀ ni yóò ti bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn..
wikipedia
yo
tí èdèàìyédè bá ṣẹlẹ̀ nínú ilé, bàbá ni yóò kọ́kọ́ parí rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí kò bá rí i yanjú ni yóò tó gbé e lọ sí ọ̀dọ̀ Mọ́gàjí agbo-ilé..
wikipedia
yo
Agbo-ilé ni ìdílé bíi mẹ́rin lọ sókè tó wà papọ̀ ní ojú kán náà..
wikipedia
yo
Àdúgbò ní àwọn agbo-ilé oríṣìíríṣìí tí ó wà papọ̀ ní ojúkan..
wikipedia
yo
A tún máa ń rí àwọn baálẹ̀ ìletò pàápàá tí wọ́n jẹ́ aṣojú fún ọba ìlú ní agbègbè wọn..
wikipedia
yo
Ejò tí wọn kò bá rí ojúùtú sì ni wọ́n máa ń gbé lọ sí ọ̀dọ̀ ọba ìlú..
wikipedia
yo
Ọba ni ó lágbára jù ninu àkàsọ̀ ìṣàkóso ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Èkejì òrìṣà ọba yìí ni àwọn ìjòyè tí wọ́n jọ ń ṣèlú..
wikipedia
yo
A rí àwọn olóyè bí Ìwàrẹ̀fà, ní Ọ̀yọ́ ni a ti ń pè wọ́n ní Ọ̀yọ́-onírúurú..
wikipedia
yo
A rí àwọn ìjòyè àdúgbò tabi abúlé pàápàá tí ó máa ń bá ọba ṣe àpérò tabi láti jábọ̀ ìlọsíwájú agbègbè wọn fún un..
wikipedia
yo
Ètò òṣèlú wa tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ yìí ni ó mú kí ó ṣòro fún àwọn òyìnbó láti gàba tààrà lórí wa (inDirect Ru)..
wikipedia
yo
Àwọn ọba ati ìjòyè wa náà ni wọ́n ń lò láti ṣèjọba lórí wa..
wikipedia
yo
Guinea-Core Beerṣeba.Ọtí ìrèké Sweet Wine, sugar-cane Beerṣeba.Ọtí kíkan, n..
wikipedia
yo
different, alone, separate ọ̀tọ̀ ni bàtá yìí yàtọ̀ (This shoe is different.)Ọ̀tọ̀ ìlú, n..
wikipedia
yo
Newness, Freshness, novelty, New, Fresh, recent, novel..
wikipedia
yo
An animal resesinmi the dog, which climbs the tree with its face, downwards, and its hind legs topmost, tree-bear.òwe, n..
wikipedia
yo
A club or a company summoned to assist one of their number in Manual Labour..
wikipedia
yo
I asked them for assistance with my farm-work.Òwenga, n..
wikipedia
yo
name gbangba Applied to Sierra Leonean immigrants, probably suggested the Plentyfulness of ‘WFDA6 a species of fish common in Sierra Leone..
wikipedia
yo
fòyà, respect (he shows Rosary to his parents.) ó fi ọ̀wọ̀ fún àwọn òbí rẹ̀.Owó, n..
wikipedia
yo
vengeance, retaliation, rẹ̀àjàràńṣe, blame; a Weaver..
wikipedia
yo
Wáges, Salary, hire, pay, stipend, an animal which is also called ‘me,’ hedgehog, bush pig..
wikipedia
yo
(His wages are ten naira per week.) owo oya rẹ̀ jẹ́ naira mẹ́wàá lọ́sẹ̀.Ọya, n..
wikipedia
yo
wife of Ṣàngó, to whom the river Niger is dedicated, hence the river is called ‘odò Ọya’ after her.Ọya, ń..
wikipedia
yo
knife used for Incising palm-trees for obtaining palm-wine.ọ̀yájú, n..
wikipedia
yo
Ọ̀yàyà, ń Merry MOOD and BehaIniti, Chèèfulness, Vivcity..
wikipedia
yo
The Harmattan, the Cool wind that blows in West Africa during December.Oyin, n..
wikipedia
yo
A title of respect conèémí on the leading elders of ọ́yóòyun, ètùtù, ẹ̀ẹ̀tu, n..
wikipedia
yo
(Primary idea, "To make to feel, suffers, etc.”, extensively used in Composition), to kill, to Murder, to put out of exis-persona, to ruin, to stay, to betray to quench fire, to extingush, to bruise, to g, to scg, to cut yam or calabash into halves, to break any hard nut, to Peel the bark of a tree, to win a game, to hatch, (eggs), to tell fables, to be intoxicated (as with liquor). [ ADV..
wikipedia
yo
To avoid giving occasion for quarrel, to avoid strife..
wikipedia
yo
Ó pa èṣù (pàáṣú/pé) Mo nilẹ̀ (hehe guguìded strife.) v.I.
wikipedia
yo
(The will reFund the cost of the book.)Pada sẹ́yìn, V.I..
wikipedia
yo
Ó pada sẹ́yìn sí àwọn ìwà burúkú rẹ̀ àtijọ́ (he laranised into his old bad habits.)pada sí v.T..
wikipedia
yo
To resort to, to come back to, to turn upon, to return to..
wikipedia
yo
Jẹ́ kí a pàdé ní ilé rẹ̀ lálẹ́ (Let Us Meet at Your House Toñight.)pade, V.t..
wikipedia
yo
To meet in battle, to encounter) wọ́n pàdégun (they met in battle).pàdéminigbọnwọ́, n..
wikipedia
yo
(poor People Can Aford Only Watery Source.)pade, V.T..
wikipedia
yo
To expose near the gate of a town or village the Garments or other clothes left by a hunter after his death.pàdémolówó, v.T..
wikipedia
yo