cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Awon ami ami mẹtẹẹta naa ni ibi ti Erin fi ese te Igbo nla odo leyin igba ti o ti rin títítí ni o wa de ibi ti Ifa ti so tele fun un..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó rí odò, ó kígbà pé “Omi o” ibí ni orúkọ ìlú náà “ọmú” ti jáde..
wikipedia
yo
olùOlùmọ rìn ṣíwájú diẹ̀ kúrò níbi odò yìí pẹ̀lú àwọn ẹ̀nìyàn rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó dé ibìkan, ibí yìí ni òun ati àwọn tí ó ń tẹ̀lé kọ́ ilẹ̀ sí..
wikipedia
yo
Ibi tí ó kọ́ ilé sí yìí ni ó pè ní “Ilémọ́” orúkọ ilé yìí “Mo” wà ní ọmú òkè títí di òní..
wikipedia
yo
Olùmòya gboro sí ìfà lẹ́nu, ó sọ odò náà ní “Ọ̀dọ́-igbó” àti ibi tí ó ti rí ẹsẹ̀ erin ní “Erin” 🙂
wikipedia
yo
Akíkanjú àti alágbára ọkùnrin ni Olùmòya ó kó àwọn ènìyàn rẹ̀ jọ..
wikipedia
yo
Ó kọ́ ilé òrìṣà kan tí ó pe orúkọ òrìṣà yìí ní “Ìpara era”
wikipedia
yo
Báyìí ni olùkalẹ̀ di Ọlọ́múwọ àkọ́kọ́ ti ìlú omuwó tí a mọ̀ sí ọmúo-òkè ní oní.Àwọn ìtọ́kasíÌpínlẹ̀ Èkìtì yí ó kí nṣe ìtàn ìlú Ọ̀rà Ò Òkè ni ẹkùn rẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìlú ọmúó òkè ni ó jẹ́ ìlú kan tí wọ́n lé kúrò ní orí ilẹ̀ tiwọn tẹ̀dó sí ní agbègbè Iyàgbà ní Ìpínlẹ̀ kogi..
wikipedia
yo
Lílé tí wọ́n lé wọn yí ni ó ṣokùnfà bí wọ́n ṣe wá sí'lu ọmúọ Ekiti nígbà náà..
wikipedia
yo
Èyí lọ́mú kí wọ́n tan ọba tí ó wà lórí ìtẹ́ nígbà náà ati àwọn ìjòyè ọmúó Èkìtì..
wikipedia
yo
Bayi ni awon igbimo wonyi fun awon ara iya yi ni ile ti o ko gun si ilu ilamọye ni ipinle kogi (ibíyí ni ọmúo npeni igun {Edge)..
wikipedia
yo
Ọlọ́múó igbana ni ó sọ fún wọn pé ọmúo òkè níwọ̀n ó máa jẹ́..
wikipedia
yo
Sihaba ni orúkọ oyè ti Ọlọ́múó ìgbàanì fún ẹni tí yíò dúró gẹ́gẹ́ bíi olórí fún wọn..
wikipedia
yo
Àdúgbò (Quarters) ni Oọmu Òkè jẹ́ N'Ìlú Oọmu.Àwọn àdúgbò tí ó wà n'ìlú Oọmu Èkìtì Ni;Ilisa, Iroko, Ijero, Afọkàn, Èdugbé, Eèkuru, Dobawá, èhù, Ìlọ́rọ̀, Oroko,ju, Oẹ̀rẹ̀, Odú, Ọ̀gun Odò, Aralayé, Agúnlẹ̀gúnlẹ̀, Olùgun-Ọ̀-Òkè
wikipedia
yo
Èdè Yorùbá ni èdè tí ó jípòpọ̀ gbogbo ọmọ Káàárọ̀-oò-jíire bí, ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà Kwa nínú ẹbí èdè Niger-Congo..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀-oòrùn Aláwọ̀-dúdú fún ẹgbẹẹgbẹ̀run ọdún..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ bí èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ọ̀kan pàtàkì lára àwọn èdè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwọn olùṣọ́ èdè Yorùbá nílẹ̀ Nàìjíríà ni ìpínlẹ̀ Edo, ìpínlẹ̀ Òndó, ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ìpínlẹ̀ Èkó, àti ìpínlẹ̀ Ògùn..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀ a tún rí àwọn orílẹ̀-èdè míràn bí Togo apá kan ní Gúúsù ilẹ̀ Amẹ́ríkà bí i Cuba, Brasil, Haiti, Ghana, Sierra Leone,United Kingdom àti Trinidad, gbogbo orílẹ̀-èdè tí a dárúkọ wọ̀nyí, yàtọ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òwò ẹrú ni ó gbé àwọn ẹ̀yà Yorùbá dé ibẹ̀.Èdè Yorùbá jẹ́ èdè kan tí ó gbalẹ̀ tí ó sì wuyì káàkiri àgbáyé..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ fún wa pé ìbátan Kwa ní èdè Yorùbá jẹ́, Kwa jẹ́ ẹ̀yà kan ní apá Niger-Congo..
wikipedia
yo
A lè sọ pé àwọn tí wọ́n ń sọ èdè Yorùbá yàtọ̀ sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà le ní ọgbọ́n miliọ̀nun tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ.Ọ̀nà tí èdè Yorùbá pín sí èdè Yorùbá gbajú-gbajà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti káàkiri nláńlá ayé lápapọ̀..
wikipedia
yo
Lílo Àmín ohun (tqaosani`ìlò-ìlò-èdè Yorùbálára àwọn èròǹgbà kan gbòógì tí ìlò èdè Yorùbá yìí ni pé mo fẹ́ kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ èdè Yorùbá lò dáradára nítorí náà a wo ìjúbà ní àwùjọ Yorùbá, a wo ààtò, Ìtúmọ̀, ìlò, àti àgbéyẹ̀wò àwọn òwe, àkànlò èdè àti ọ̀rọ̀ àmúlò mìíràn..
wikipedia
yo
A wo èdè àmúlò nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀ àti ìgbà tí a bá kọ èdè Yorùbá sílẹ̀..
wikipedia
yo
A si wo ìlànà ati òté to de sísọ̀rọ̀ ni àwùjọ Yorùbá..
wikipedia
yo
A wo bi a se n se agbekale ise to da le girama, iwe atumọ, ọ̀rọ̀ àpilẹ̀kọ, àbọ̀ ìpàdé, ìjábọ̀ ìwádìí, ìwé ìkéde pélébé àti èyí ti a fi n se ìpolongo ti a máa ń tẹ̀ mọ́ ara ògiri..
wikipedia
yo
Ó yẹ ki a mọ ọ̀rọ̀ sọ, ki a si mọ ọ̀rọ̀ ọ́ kọ sílẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí a bá ka ìwé kékeré yìí.Bí èdè Yorùbá ṣe di kíkọ sílẹ̀kí àwọn Òyìnbó tó gòkè odò dé, kò sí ètò kíkọ àti kíka èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Gbogbo ọ̀rọ̀ àbáláyé tí ó ti di akọ sílẹ̀ lóde òní,nínú ọpọlọ àwọn baba ńlá wa ni wọ́n wà tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Irú àwọn ọ̀rọ̀ àbáláyé báyìí a máa súyọ nínú orin, ewì àti ìtàn àwọn baba wa..
wikipedia
yo
Nígbà tí a kọ ń pe gbogbo àwọn ẹ̀yà tí èdè wọn papọ̀ yìí ni Yorùbá tàbí Yóòbá, wọn kò fi tara tara fẹ́ èyí nítorí pé àwọn ẹ̀yà Yorùbá ìyókù gbà pé àwọn Ọ̀yọ́ nìkan ni Yorùbá..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn òjíṣẹ́ Ọlọ́run aláwọ̀ funfun tó wá wàásù nípa kírísítì ṣe àkiyèsí pé èdè wọn bá ara wọn mu ni wọ́n bá pè wọ́n ní Yorùbá tàbí Yoòbá..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá ti a kò l'éní lo si ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí a sì wá dá padà sí Saró lẹ́hìn tí òwò ẹrú ti tán ni àwọn òyìnbó Ìjọ C.M.S..
wikipedia
yo
kọ́kọ́ sọ di onigbagbọ.Àbùdá èdè YORÙbaàBúdà èdè Yorùbá ni ó máa jẹ́ kí a mọ ohun tí èdè jẹ́ gan-an..
wikipedia
yo
Èdè Yorùbá kógo àbùdá wọ̀nyí já.(1) Ohun tí a bá pè ní mi gbà tó aobdubdi lnfṣePẹ̀lú Gibh Knjẹde gbọ́dọ̀ jẹ́ ohun tí a fi ìró èdè gbé jáde..
wikipedia
yo
A ó ṣe àkíyèsí pé èyí yàtọ̀ sí pípòòyì, ijó ọlọ́bọ̀ùnbọ̀un, dídún tàbí fífò tata tàbí jíjuwó alákàn sí ara wọn.(2) Èdè nílò kíkọ́ ó fún ìgbà pípẹ́ díẹ̀ kí ènìyàn tó lè sọ ọ́..
wikipedia
yo
Ó ti di bárakú tàbí àṣà fún wa pé a gbọ́dọ̀ kọ́ ọmọ tí a bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bí ní èdè..
wikipedia
yo
Àkíyèsí ati iwadii yii ni awon Ẹlẹ́dẹ̀ Gẹẹsi n Gofe si nigba ti awon ba so pe "language is culturally transmitted"
wikipedia
yo
Ọmọ tí a bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bí tí a kò kọ́ ní èdè, àti àwùjọ jẹ́ kòríkòsùn.(3) ìhun ní èdè ènìyàn gùn lé tàbí dálé..
wikipedia
yo
Bí a ṣe hun ọ̀rọ̀ pọ̀ nínú gbólóhùn ṣe pàtàkì kíka iye ìró èdè nínú gbólóhùn kò fi ibì kankan ní ìtumọ̀.A lè sọ pé ìyàndá ṣubúIyanda ẹlẹ́mu ṣubúó ṣubúIyanda tí a ti sọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣubú.Ìyípadà orírsirísi ló le wáyé sí gbólóhùn wọ̀nyí tí yóò sì da ètò wọn ní, síbẹ̀síbẹ̀, yóò ní ìtumọ̀..
wikipedia
yo
Irú àbùdá yìí ni onímọ̀ ẹ̀dá-èdè ń pè ní “Structure dependence”.4) Gbogbo èdè kọ̀ọ̀kan ló ní àwọn ìró èdè tirẹ̀ tí a ń pè ní (fóníìmù {phonemes})..
wikipedia
yo
Foniimu yìí sún mọ́ ti àwọn ẹranko ṣùgbọ́n ó sì tún rọ̀ jut i ẹranko lọ..
wikipedia
yo
kì í dá ìtumọ̀ ní kó wúlò ìgbà tí a bá kàn án pọ̀ mọ́ fóníìmù mìíràn gan-an ló máa ṣìṣẹ́..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ àkíyèsí àti ìwádìí yí ni àwọn onímọ̀ ẹ̀dá-èdè ń pe Gẹ̀ẹ́sì rẹ̀ ní “Conkú” tàbí “double irú” ìwádìí fihàn pé àwọn ẹyẹ àti ẹranko tí wọ́n ní ìró èdè kò pọ̀, iye èdè tí ọ̀kọ̀ọ̀kan ní kò pọ̀ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ adìyẹ ní ìró èdè bí Ògún, tí mààlúù jẹ́ mẹ́wàá ṣùgbọ́n kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ ní ọgbọ̀n.(5) Èdè jẹ́ ohun ètò tí a máa ń lò láti ṣe àròyínlé.Ìwúlò èdè Yorùbá Èdè wúlò fún kí a lè bá ara sọ ọ̀rọ̀ léyìí tí gbédìí fún ẹwà akéwì náà..
wikipedia
yo
A kò lè ṣe kí a má kí ara wa ní orísirísi ọ̀nà bóyá ọ̀rẹ́ sí ọ̀rẹ́, pẹ̀lú orísirísi ẹwà èdè.
wikipedia
yo
Èdè wúlò fún fífi sọ èrò ọkàn wa àti fífi ìtara hàn sí ohun tí a gbọ́ rí tàbí tí ó ṣẹlẹ̀ sí wa..
wikipedia
yo
Àṣà Yorùbá jẹ́ ọ̀nà ti àwọn ẹ̀yà [Yorùbá] ń lò láti fi gbé èrò, ìmọ̀, àti ìṣe wọn kalẹ̀ tí ó sì bá àwùjọ wọn mu ọ̀nà tí ó gún gẹ̀gẹ̀..
wikipedia
yo
Tàbí kí a sọ wípé àṣà ni ohun gbogbo tó jẹ mọ́ ìgbé ayé àwọn ènìyàn kan, ní àdúgbò kan, bèrè lórí èrò, èdè, ẹ̀sìn, ètò ìṣèlú, ètò ọ̀rọ̀ ajé, ìṣẹ̀dá ohun èlò, ìtàn, òfin, íṣe, ìrísí, ìhùwàsí, iṣẹ́-ọ̀nà, oúnjẹ, ọ̀nà iṣẹ́ nǹkan, yíyí àyíká tàbí àdúgbò kọ̀ọ̀kan padà..
wikipedia
yo
Pataki Jùlọ ẹ̀sìn ìbílẹ̀, eré ìbílẹ̀, ati iṣẹ́ ìbílẹ̀..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ni wọ́n kó’rà jọ pọ̀ ń jẹ́ àṣà..
wikipedia
yo
Bí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa àṣà àti ìṣe Yorùbá, a ń sọ̀rọ̀ lórí àwọn ohun tí a ń mú ẹnu bá ní ìhùwàsí àti ìrísí wa láàrín àwùjọ..
wikipedia
yo
Nínú ogún-lọ́gọ̀ àwọn àṣà àti iṣẹ́ tí ó ń bẹ nílẹ̀ Yorùbá, ọ̀kan pàtàkì ni' Àṣà ìkíni nílẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Èyí jẹ́ ohun tí gbogbo àwọn ẹ̀yà tí ó kù ní àgbáyé fi ma ń dàyanrí ọmọ kòkún-ọ kò-jíire bí tòótọ́ ni gbogbo ayé tí wọ́n bá dèé jẹ́ kí a jọ gbé e yẹ̀wò, kí a jọ yàn-án-náà rẹ́..
wikipedia
yo
O ní í ṣe pẹ̀lú ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní déédé àsìkò náà..
wikipedia
yo
bí ó sì jẹ́ àṣálẹ́, “Ẹ kú lẹ́ alẹ́/ẹ-Lá ni a ń kí'ni àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Nílẹ̀ Yorùbá, gbogbo àsìkò ni ó ni ìkíni tirẹ̀, ṣùgbọ́n ọmọdé ni ó kọ́kọ́ máa ń ki àgbà..
wikipedia
yo
Èyí tí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, ìgbàgbọ́ Yorùbá ni wí pé Irú ọmọ bẹ́ẹ̀ kọ́ ni ẹ̀kọ́ tàbí, wọ́n kọ́ ọ ni'lé, kò gba ni..
wikipedia
yo
Bí ó bá jẹ́ ìgbà ayẹyẹ bíi ìsìnkú àgbà, nítorí Yorùbá kì í ṣe òkú odò, ẹ̀hìnkùnlé ni wọ́n máa ń sin òkú odò sí..
wikipedia
yo
Igbagbọ wọn ni pé, òfo ni ó jẹ́ fún àwọn òbí irú ẹni bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Wàyí, bí ó bá jẹ òkú àgbà, wọn á ní, “Ẹ kú ọ̀fọ̀, ẹ kú ìsìnkú, Ọlọ́run yóò mú ọjọ́ jìnnà sí’rà ọ́.” Bí ó bá jẹ́ ayẹyẹ ìkómọjáde/ìsọmọlórúkọ, wọn á ní, “Ẹ kú owó o.” Bákan náà, oríṣiríṣi àkókò ni ó wà nínú ọdún..
wikipedia
yo
Àkókò ọ̀fìnkìn, àkókò oyè, àkókò oorun (Summer), àkókò òjò, gbogbo wọ̀nyí sì ni àwọn Yorùbá ni bí a ṣe ń kí'ni fún..
wikipedia
yo
Ẹ jẹ́ kí a gbé àṣà ìsìnkú yẹ̀wò.Àṣà ìsìnkú nílẹ̀ Yorùbá gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú wípé ó ní àwọn òkú tí Yorùbá máa ń ṣe ayẹyẹ fún, àwọn bíi òkú àgbà, nítorí wọ́n gbà wí pé, olóògbé ló sinmi ni, àti wí pé, wọ́n lọ'lé..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ pé, ọjà ni ayé, ṣùgbọ́n ọ̀run ni ilẹ̀..
wikipedia
yo
Bí ó bá jẹ́ òkú ọ̀dọ́ tàbí ọmọdé, òkú ọ̀fọ̀ àti ìbànújẹ́ ló jẹ́..
wikipedia
yo
Yorùbá maa n na owo ati ara si isinku Agba, paapaa bi Oloogbe naa ba jẹ ẹni ti o ni ipo ati ọlá nigba ti o wa láyé, ti o si tun bi ọmọ..
wikipedia
yo
Ìsìnkú àwọn wọ̀nyí máa ń lárinrin, ayé á gbọ́, ọ̀run á sì tún mọ̀ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ni ayé àtijọ́, bi aláwọ̀ bá kú, àwọn àwọn olùwo ní ń sìnkú irú ẹni bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Wọn a pa adìyẹ ìrànà, wọ́n a sì máa tú ìyẹ́ rẹ̀ bí wọ́n ṣe ń gbé òkú rẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Leyin ti won ba sin oku tan, awon alawo naa a sun adiyẹ naa je..
wikipedia
yo
Ìdí rèé tí Yoòbá fi máa ń sọ wí pé, “Adìyẹ ìrànà kì í ṣ’ọ̀hún á jẹ́ gbé.” Nítorí pé, kò sí ẹni tí kò ní kú..
wikipedia
yo
Òfo ni ó máa ń jẹ́ ti iyawo ilẹ̀ bá ṣáájú ọkọ rẹ̀ kú..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ pé, ọkọ ló máa ń ṣáájú aya rẹ̀ kú, kí ìyàwó máa bójú tó àwọn ọmọ..
wikipedia
yo
Fún ìdí èyí, bí ọkùnrin bá kú, àwọn ìyàwó irú ẹni bẹ́ẹ̀ máa ṣe opó pẹ̀lú ìlànà àti àṣà Yorùbá..
wikipedia
yo
Ogójì ọjọ́ tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ni wọ́n máa ń fi ṣe opó..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìsìnkú, àwọn àgbà ilẹ̀ ni wọ́n máa pín ogún olóògbé fún àwọn ọmọ rẹ, bí ó bá jẹ́ òkú ọlọ́mọ..
wikipedia
yo
Àmọ́ tí kò bá bí'mọ́, àwọn ẹbí rẹ̀, ní pataki jùlọ, àwọn ọmọ ìyá rẹ̀ tí ó jù ú lọ ni wọ́n máa pín ogún náà láàárín ara wọn..
wikipedia
yo
O tun jẹ aṣa Yoruba Òmíì ki wọn maa su opo oloogbe fun awon aburo rẹ, lati fi se aya.Ohun ti o je orírun asa ni 'Ara', o le dara tabi ki o buru..
wikipedia
yo
Ìpolówó Èkìtì - iyán rere, ọbẹ̀ rere; ìpolówó Òndó Ẹ̀gi - (dípo iyán) Ẹ̀bà gbọ̀n fée..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ kúndùn Ẹ̀bà, Ìlàjẹ fẹ́ràn Olùru, Igbo Oté kìí sí í fi Láfún òṣèré..
wikipedia
yo
(ẹ) A kò mọ ìtumọ̀ àròkọ tí à ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́.(ẹ) a kò fi èdè abínibí wa kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́.Àwọn ọ̀nà tí àṣà máa ń gbà yípadà(a) bí àṣà tó wà nílẹ̀ bá lágbára ju èyí tó jẹ́ tuntun lọ, èyí tó wà tẹ́lẹ̀ yóò borí tuntun..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, aṣọ wíwọ̀.(b) Àyípadà lè wáyé bí àṣà tó wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀ bá dọ́gba pẹ̀lú àṣà tuntun, wọ́n lè jọ rìn pọ̀..
wikipedia
yo
(d) Bí àṣà tuntun bá lágbára ju èyí tó wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀, yóò sọ àṣà ti àtẹ̀hìnwá di ohun ìgbàgbé..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kan náà ni wọ́n délé ayé nítorí pé kò sí ohun tí a fẹ́ sọ nípa àṣà, tí kì í ṣe pé èdè ni a ó fi gbé e kalẹ̀..
wikipedia
yo
A lè fi èdè Yorùbá sọ ohun tó wà lọ́kàn ẹni, a lè fi kọrin, a le fi kéwì, a lè fi jọ́sìn, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Láti ara àwọn nǹkan tí a ń sọ jáde lẹ́nu wọ̀nyí ni àṣà wa ti ń jẹyọ..
wikipedia
yo
Ara èdè Yorùbá naa ni òwe ati àwọn àkànlò-èdè gbogbo wà..
wikipedia
yo
A lè fa púpọ̀ nínú àwọn àṣà wa yọ láti ara ÒWE àti ìjígún èdè..
wikipedia
yo
Àti wí pé, òun ni ó fà á tí ó fi jẹ́ pé, bí àwọn ọmọ Odùduwà ṣe tàn kálẹ̀, orílẹ̀-èdè kan ni wọ́n, èdè kan náà ni wọ́n ń sọ níbikíbi tí wọ́n lè wà..
wikipedia
yo
Fún ìdí èyí, láìsí ènìyàn, kò le è sí àṣà rárá.Àṣà jẹ́ nǹkan gbòógì fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ṣùgbọ́n àwọn Yorùbá mú ní ọ̀kúnkúndùn kí gbogbo wa sì gbé lárugẹàwọn ìtọ́kasí 1.Adéoyè C.l..
wikipedia
yo
(1979) Àṣà àti iṣé Yoruba Oxford University Press Limited 2.J.A..
wikipedia
yo
Atanda (1980) an Introduction to Yorùbá History Ìbàdàn University Press Limited 3.Adeọ Fafásìku (1995) Igbajo And Its People printed By Writers Press Limited 4.G.O..
wikipedia
yo
Olusanya (1983) Studies in Yoruba History And Culture Ìbàdàn University Press Limited..
wikipedia
yo
Samuel Johnson (1921) The History of the Yorùbás A diVisional of CSS Limited...
wikipedia
yo
Ṣe Yorùbá bọ̀ wọ́n ní “Ṣe bó o ti mọ ẹlẹ́wàa Ṣàpọ́n..
wikipedia
yo
Ìwọ̀n eku nìwọ̀n ìtẹ́." Wọ́n a a sì tún máa pa á lówe pé “Ìmọ̀ ìwọ̀n ara ẹni ní ìlẹ̀kẹ̀ ọgbọ́n nítorí pé ohun ọ̀wọ̀ mi ò tó ma fi gọ̀gọ̀ fà á, ì ì já lu olúwarẹ̀ mọ́lẹ̀ ní” ayé òde òní, àwọn ọ̀dọ́ tilẹ̀ máa ń dáṣà báyìí pé “déédéé rẹ̀, Ìgbéraga ní ìgbérasàn lé.” Wọ́n máa ń sọ èyí fún ẹni tí ó bá ń kọjá ààyè rẹ̀ ni..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ ọgbọ́n kan ṣe wí pé “Ní àtètèkọ́ṣe ni ọ̀rọ̀ wà,” Bẹ́ẹ̀ náà ni ètò ti wà fún ohun gbogbo láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ wá..
wikipedia
yo
Adilọ́rọ̀ baba tó ju baba lọ tún fi ààlà sáàárín ilẹ̀, omi Òkun, àti sánmọ̀..
wikipedia
yo
ẹlẹ́tọ́ lọ́ọ́lọ́run gan-an.Kiní ètò? Ìtọ̀ jẹ́ ọ̀nà tí à ń gbà láti ṣàgbékalẹ̀ ohun kan tàbí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan lójuna àti mú kí ó ṣe é wò tàbí kó ṣe é rí tàbí kó dùn ún gbọ́ sétí..
wikipedia
yo