cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
àkòkò tí ọkùnrin tàbí obìnrin ti dàgbà tán.Public, adj..
wikipedia
yo
(he talked about the publication of his first book.) Ó sọ̀rọ̀ nípa ìtẹ̀jáde ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́.Publicly, ADV..
wikipedia
yo
Ní gbangba (it was announced publicly.) wọ́n kéde rẹ̀ ní gbangba.Publish, v.t..
wikipedia
yo
(They published Yorùbá books.) Wọ́n tẹ àwọn ìwé Yorùbá fún títa.publisher, n..
wikipedia
yo
(He pufẹ́f smoke into my face.) ó fẹ́ èéfín jáde sí mi lójú.púgilist, n..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó ń fi ìkùukùu jà, ẹni tí ó ń kan ẹsẹ̀púräcious, adJ..
wikipedia
yo
(He is a puräcious man.) Oníjà ọkùnrin ni.puräcity, n..
wikipedia
yo
Ohun ẹ̀rọ láti fi gbé ohun tí ó wúwo sókè.Pulpit, n..
wikipedia
yo
(The plan was condemned from the Pulpit.) won bu enu ate lu ero naa lati ori aga iduro iwaasu.pulc, v.t..
wikipedia
yo
Lu Kìkììkì (he has a púlsating headache.) Orí fífọ́ rè n lu kìkìíkìPulse, n..
wikipedia
yo
Ìlú kíkí ti ọ̀kan, ẹwà (The doctor felt his Pulse.) Dókítà yẹ ìlú kíkí ọkàn rẹ̀ wò..
wikipedia
yo
Gun kúnná, lọ (he pulverí Bnesneste.)Ó gun àwọn egungun kúnná.Filistini, n..
wikipedia
yo
(The Jesuní was used for Pumping water out of the well.) Wọ́n ń lo ẹ̀rọ náà láti fa omi sókè láti inú kànga..
wikipedia
yo
(He bought a hole Punch.) O ra irin-inse ilu Ihò.Punch, V.t..
wikipedia
yo
(She Punched him on the nose.) Ó kàn án ní ẹsẹ̀ ní ìmú.Punctilious, adj..
wikipedia
yo
Kíyè sí nnken kínníkínní (he was a punctilious host.) olugbalejo tí ó máa ń kíyè sí nnkenken kínníkínní ni.únKódà, adj..
wikipedia
yo
Ṣe ni àkọ́kọ́, ṣé gẹ́ẹ́ (she has been punctual) ó ti máa ń ṣe nǹkan ní àkókò.Puneṣinṣintiwọn, n..
wikipedia
yo
Lákòókò gan-an (they always pay Puncségesège.) wọ́n máa ń sanwó lákòókò gan-an.únìmọ̀tẹ, v.t..
wikipedia
yo
Fi àmì sí ìwé kíkà, bí àpẹẹrẹ “Àmì ìdánudúró, Petkàyéfì, N..
wikipedia
yo
(The Benjamini has Puncalitieli) nnkan ti gun táyà náà.Pungent, adj..
wikipedia
yo
(he bought a Pangent Sro.) O ra aáṣáà tí ó mu.lẹ́wà, V.t..
wikipedia
yo
Níyà, ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́ (he was Òmìnira for coming to school late.) Wọ́n jẹ ẹ́ níyà fún pípẹ́ dé ilé-ẹ̀kọ́.punishment, n..
wikipedia
yo
Ìyà, Ìjìyà, (What is the punishment for Murder?) kí ni ìjìyà fún ìpànìyàn?.Punt, N..
wikipedia
yo
(The Lamb was a Puny little thing.) Aláìlera ni ọ̀dọ́ aguntan náà..
wikipedia
yo
Ọmọ ile-eko, akekoo (How many Ppils does the school have?) akẹ́kọ̀ọ́ mélòó ni ilé-ẹ̀kọ́ náà ni? pupil-teacher, n..
wikipedia
yo
(He is a pupil-teacher.) Tíṣà Kékeré tí ó ń kọ́ iṣẹ́ lábẹ́ẹ tíṣà àgbà ni..
wikipedia
yo
Ọmọ ajá (he bought a Puppy) ó ra ọmọ Ajá Ken.purchase, V.T..
wikipedia
yo
Ra (they purchased the land for ń 100,000.) Wọ́n ra ilẹ̀ náà ní ẹgbẹrun lọ́nà ọgọrun-un naira..
wikipedia
yo
(he filled his car with his purchases.) Ó kó àwọn ohun tí ó rà kún inú káà rẹ̀pẹ̀lú] ń olùrà..
wikipedia
yo
(He bought a bottle of pure water.) Ó ra ìgò omit í ó mọ́ kan.purgé, v.t..
wikipedia
yo
We mọ́, we (he was purged of sins.) Wọ́n wẹ̀ ẹ́ mọ́ kúrò ninu ẹsẹ̀Purikáàárẹ̀, n..
wikipedia
yo
Ìwẹ̀nùmọ́ (He bought a water sókèakọ̀wé plant.) Ó ra ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń ṣe ìwẹ̀nùmọ́ omi.Ahasaya,fier, ń..
wikipedia
yo
We mọ́, sọ di mímọ́ (One tablet will Purify the water in 10 minutes.) Lógún oníhóró Ken yóo sọ omi yẹn di mímọ́ ní ìṣẹ́jú mẹ́wàá.purity, n..
wikipedia
yo
Mímọ́, ìwà mímọ́ (they tested the purity of the water.) Wọ́n yẹ mímọ omi náà wò.Alábùkúnloin, V.t..
wikipedia
yo
Jí jalè, (We purloined a couple of old computers from work.) A jí àwọn kọ̀ǹpútà mélòó kan tí ó ti ọ̀gbọ̀ láti ibi iṣẹ́ purloiner, n..
wikipedia
yo
(That is a Purple flower.) adọ̀dọ́ aláwọ̀ àlùkò nìyẹn.purport, n..
wikipedia
yo
(What is the purport of what he yàgò?) Kí ni ìtumọ̀ ohun tí ó sọ?purpose, ń..
wikipedia
yo
(Our campaign's main purpose is to raise money.) Ètè ìpolongo wá ni láti kó ọwọ́ jọpurpose, V..
wikipedia
yo
(They purpose to make a further attempt.) wọ́n pète láti gidánwò sípurpurpọ̀?amí, ad..
wikipedia
yo
Àṣedànù, láìní anfaani, láìní ète, láìní ìpinnu, aláìní anfaani..
wikipedia
yo
(It was a purpogbòde destruction.) Ìparun aláìní anfaani ni.purr, V.T.and I..
wikipedia
yo
kún bí olôògínnì (he purred with satisfaction.) ó kún bí ìgbàlàní fún ìdùnnú.pur, n..
wikipedia
yo
(I took ten naira out of my purse.) Mo mú naira mẹ́wàá jáde láti inú àpò owó mi.purser, n..
wikipedia
yo
Ìlépa, ìtẹ́lẹ̀ (she traveled to Ibadan in pursuit of Hepbray.) Ó rin ìrìnàjò lọ sí Ibadan fún ìlépa ìdùnnú.)puryékéyékéce, n..
wikipedia
yo
Ṣàngó Olúkósọ́tọ̀, òkò Ọya.Òrìṣà Ṣàngó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn òrìṣà tí àwọn Yorùbá ń bọ..
wikipedia
yo
Ṣàngó jẹ́ òrìṣà takuntakun kan láàárín àwọn òrìṣà tókù ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ òrìṣà tí ìran rẹ̀ kún fún ìbẹ̀rù, ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbẹ̀rù nígbàtí ó wà láyé nítorípé ènìyàn là gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó di òrìṣà àkúnlẹ̀bọ..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ wí pé ọmọ ọ̀ranyàn ni Ṣàngó ń ṣe àti pé ọ̀yà, Ọ̀ṣun àti ọba ni wọ́njẹ́ ìyàwó rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìhùwàsí búburú àti dídá wàhálà àti ìkọlura pẹ̀lú Ìjàyè fàmílétè-kí-n-tutọ́ pọ̀ lọ́wọ́ Ṣàngó gẹ́gẹ́ bí ọba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di ọ̀tẹ̀yíMika, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtẹ̀ mọ́ ọ..
wikipedia
yo
orógbó náà sì ni a máa ń lò ní ojúbọ Ṣàngó títí di òní..
wikipedia
yo
Gírámà èdè Yorùbágirama ni ìmọ̀ nípa bí a ṣe ń lo àwọn ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ètò àti ìlànà ní èdè Yorùbá ìsọ̀rí gírámà ni wọ́n yìí (a) ọ̀rọ̀ orúkọ (b) ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ (d) ọ̀rọ̀ arọ́pò àfarajórúkọ (ẹ) ọ̀rọ̀ ìṣe (ẹ) ọ̀rọ̀ àpèjúwe (f) ọ̀rọ̀ àpọ́nlé (g) ọ̀rọ̀ atọ́kùn (gb) ọ̀rọ̀ àsopọ̀.Ojú-ìwé kìínígirama Yorùbákí ni síntáàsì? síntáàsì jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀ka gírámà èdè tí ó ní í ṣe pẹ̀lú bí a ṣe ń sọ ọ̀rọ̀ pọ̀ tí ó fi ń di gbólóhùn àti bí a ṣe ń fún gbólóhùn yìí ní ìtumọ̀..
wikipedia
yo
Nínú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí, a ó máa m ẹnu bá ohun tí a ń pè ní òfin..
wikipedia
yo
Ìtumọ̀ òfin gẹ́gẹ́ bí a ṣe lò ó ní àwọn ìlànà tí elédè máa ń tẹ̀lé nígbà tí ó bá ń sọ èdè rẹ̀ yìí yàtọ̀ sí ìlò èdè..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ èdè ni ohun ti ẹlẹ́dẹ̀ mọ̀ nípa èdè rẹ̀ ṣùgbọ́n ìlò èdè ni ohun tí ẹlẹ́dẹ̀ sọ jáde ní ẹnu..
wikipedia
yo
Ẹlẹ́dẹ̀ lè ṣe àṣìṣe nípa ìlò èdè ṣùgbọ́n èyí kò sọ pé elédè yìí kò mọ èdè rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni ènìyàn lè mú ẹmu yó tí yóò máa sọ kántankàntan..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọtí bá dá ní ojú rẹ̀, yóo sọ ọ̀rọ̀ tí ó mọ́gbọ́n lọ́wọ́.Ninu ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí, a ó mẹ́nuba ohun tí a ó pè ní Òfin..
wikipedia
yo
Ohun tí a pè ní òfin yìí ni bí elédè ṣe ń sọ èdè rẹ̀ bí ìgbà pé ó ń tẹ̀lé ìlànà kan.Bí àpẹẹrẹ rẹ̀, ẹni tí ó bá gbọ́ Yorùbá dáradára yóò mọ̀ pé (1a) ni ó tọ̀nà pé (1b) kò tọ̀nà, (1)(a) mo lọ sí oko (b)sì lọ oko mọ ohun tí eléyìí ń fi hàn wá nipé Ìlànà kan wà tí elédè ń tẹ̀lé láti sọ ọ̀rọ̀ pọ̀ di gbólóhùn..
wikipedia
yo
IRÚ gbólóhùn tí o bá tẹ̀lé ìlànà tí elédè mọ̀ yìí ni a ó sọ pé ó bá òfin mu..
wikipedia
yo
Ó yẹ kí a tètè mẹ́nu ba ìyàtọ̀ kan tí ó wà láàrín tí òfin mú àti jíjẹ àtẹ́wọ́gbà..
wikipedia
yo
(2)(A)àwọn tí ó lò kò pọ̀ (b) àwọn tí wọ́n lọ kó pọ̀ méjèèjì ni ó bá òfin mu nítorí méjèèjì ni a máa ń sọ nínú èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Ẹyẹ kò ní nnkenken kan an se pẹ̀lú pé bóyá gbólóhùn méjèèjì bófin mu tàbí wọn kọ́ Orísùn..
wikipedia
yo
Ohun ti àmì ọfà yìí ń sọ ni pé kí á tún gbólóhùn (gb) kọ́ ni àpór àti Apis..
wikipedia
yo
Abẹ́ rẹ̀ ni a ti máa ń rí ìbá (iBM àsìkò (as), múudú (m) àti ìbámu (iBM)..
wikipedia
yo
A ò mẹ́nu bá àfòmọ́ dáadáa ní iwájú ṣùgbọ́n kí á tó ṣe èyí, ẹ jẹ́ kí á sọ̀rọ̀ nípa àpòr àti Apisójú-ìwé kejìayọ̀ Bámgbóṣégirama àti gírámà YORÙbàá Bámgbóṣé (1990), Fonọ́lọ́jì àti Gírámà Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ àkọ́sọ láti ìgbà tí ìgbìmọ̀ ìwádìí ìjìnlẹ̀ Èkó (n.E.R.C.) ti gbé ìlànà ẹ̀kọ́ Yorùbá fún ìlò -ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì jáde ni ó ti di dandan láti wá ìwé tí yó ṣe àlàyé yékéyéké lórí àwọn iṣẹ́ tí ó jẹ yọ nínú ìlànà ẹ̀kọ́ tuntun yìí..
wikipedia
yo
Ìrírí wa nipé àti akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ni ó máa ń ní ìṣòro lórí iṣẹ́ tí ó bá èdè yàtọ̀ sí lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Lo ìdí nìyí tí a fi ṣe ìwé yìí lórí èdè, tí a sì lo ìmọ̀ ẹ̀dà-èdè láti fi ṣàlàyé àwọn orí-ọ̀rọ̀ fonọ́lọ́jì àti gírámà..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì àti ti Olùkọ́ni, Láìmẹ́nuba àwọn olùkọ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ bẹ́ẹ̀, ni wọ́n ti ń lo ìwé Èdè Ìperí Yorùbá ti ń.E.R.C..
wikipedia
yo
TẸ̀ JÁDE NÍ ỌDÚN 1984, tí ọ̀jọ̀gbọ́n ayọ̀ Bam sì ṣe olótùú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìwé Fonọ́lọ́jì àti Gírámà Yorùbá yìí jẹ́ ìgbésẹ̀ kejì lórí lílo èdè-ìperí Yorùbá nítorí pé a ṣe àlàyé àwọn èdè-ìperí tí ó bá ẹ̀dá-èdè lọ dáadáa; a sì lo àpẹẹrẹ oríṣiríṣi láti fi ìtumọ̀ wọn hàn kedere..
wikipedia
yo
Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi tí mo ṣe olóòtú ìwé Èdè-ìperí Yorùbá náà ni mo kọ ìwé tuntun yìí..
wikipedia
yo
Mo sì kọ́ ọ ní ọ̀nà tí yó rọrùn fún akẹ́kọ̀ọ́ láti kà nítorí pé nípa ìrírí púpọ̀ tí mo tín í nípa kíkọ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀dà-èdè Yorùbá, mo mọ ọgbọ́n tí a lè fi ṣe àlàyé àwọn orí-ọ̀rọ̀ tí ó díjú lọ́nà tí yó lè fi tètè yẹ ni..
wikipedia
yo
Nínú apẹ kìíní àti apá kejì, a pín àwọn orí-ọ̀rọ̀ sí abẹ́ orí kọ̀ọ̀kan nínú èyí tí a ṣe àlàyé àti ìtúpalẹ̀ orí-ọ̀rọ̀, tí a sì lo àpẹẹrẹ oríṣiríṣi láti fi ìdí ìtúpalẹ̀ náà gúnlẹ̀ dáadáa..
wikipedia
yo
Orí mẹrinla ni ó wà ní abẹ́ fonọ́lọ́jì, tí mejidinlogun sì wà lábẹ́ girama..
wikipedia
yo
Ó ṢEÉ ṣe fún olùkọ́ láti fa ẹ̀kọ́ méjì mẹ́ta yọ láti ara orí kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
A sì tún lè lo orí kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àtúnyẹ̀wò iṣẹ́ tí a ti ṣe kọjá lórí orí-ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Ní apá kẹ́ta ìwé yìí, a fi ìdánwò èwoní mẹ́rin nínú èyí tí ìbéèrè mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n wà nínú ìkòọkenken ṣe àpẹẹrẹ irú ìbéèrè tí a le ṣe fún gírámà àti fonọ́lọ́jì Yorùbá..
wikipedia
yo
Irú àpẹẹrẹ ìdánwò báyìí yóò wúlò fún àwọn tí ó ń Sẹ́ẹ̀tì ìdánwò àti fún àwọn olùkọ́ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà pàápàá yọ̀ lè lo ìdánwò yìí gẹ́gẹ́ bí àfikún fún ìdánrawò tí ó wà lẹ́yìn orí kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Mo ké sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ láti ran ara wọn lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́ Yorùbá..
wikipedia
yo
ọ̀ná tí wọ́n sì le fi ṣe bẹ́ẹ̀ ni kí wọ́n lo ìwé tí yó mú kí ẹ̀kọ́ Yorùbá rọrùn fún wọn láti kọ́..
wikipedia
yo
Ìwé náà sì lè fún wọn ní ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún ẹ̀kọ́ Yorùbá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga.Àwọn ìtọ́ka síèdè Yorùbá..
wikipedia
yo
CHADi (SADiFIKi)ọmọ ẹbí kan ni eléyìí jẹ́ fún ẹbí èdè Ilẹ̀ Aṣírírika kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Afro-Áàti (Afu-E-ìkì)..
wikipedia
yo
Àwọn èdè tí ó wà nínú Chadigbóṣe yìí tó ọgọ́jọ (160) àwọn tí ó sì ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí tó ọgbọ̀n mílíọ̀nù..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń sọ ó bẹ̀rẹ̀ láti iha Ariwa Ghana (Gánà) títí dé àárín ìnilè Arikafi..
wikipedia
yo
Hausa ni gbajumọ ju ninu awọn ede ti o wa ni abẹ́ ipin Chadi..
wikipedia
yo
Oun nikan ni o wa ninu ìpín yìí tí ó ní àkọsílẹ̀ tí ó péye..
wikipedia
yo
Lára àwọn èdè mìíràn tí ó wà ni ìpín yìí a ti rí Anga, kòtoko ati mubi.àwọn èdè Afrika..
wikipedia
yo
Aiku tabi akoli jẹ ẹya kan ni apa ariwa ile Uganda ati ni apa guusu ilẹ̀ Sudan..
wikipedia
yo
Elédùmarè Yorùbá gbàgbọ́ wípé Elédùmarè ni ó dá ayé àti ọ̀run pẹ̀lú gbogbo ohun tí ń bẹ nínú wọn..
wikipedia
yo
Yorùbá sí gbàgbọ́ wí pé kò sí ohun tí Elédùmarè kò le ṣe, òhun ni wọ́n fi n kí Elédùmarè wí pé “ọba àìkú, ọba àtiyín, àlàyé gbèlẹ́gbẹ́lé bí ẹní láyin, ọba àtẹ̀lé bí ẹni tẹni, Ọba àtẹ sánmọ̀ bí ẹni tẹ̀sọ, Alọ̀run-láyé-àlàyé-lọ́rùn, Olówó gbogbo tí yọ ọmọ rẹ̀ nínú òfin atẹ́rẹrẹ káríayé.” Bí a bá ti ojú inú wò ó á rí wí pé àwọn oríkì yìí túmọ̀ i Olódùmarè ṣe jẹ́ hàn láwùjọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ohun tí a ń sọ ni wí pé ọ̀pọ̀ ìtàn ìwáṣẹ̀ ló sọ wípé bí Olódùmarè ṣe dá ayé àti ọ̀run..
wikipedia
yo
Èrò Yorùbá ni pé kò síohun ti a lè fi wé elédùmarè nítorí àwọn mộmọ tàbí àbùdá rẹ̀ tó tayọ àwárí ẹ̀dá..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, Ẹlẹ́dàá, àlèmi, òun ló ni ọ̀sán ati òru, ọlọ́jọ́ òní, òní ọmọ olórin ọ̀la ọmọ Ọlọrun ọ̀tunla ọmọ olórin, iremi ọmọ olórin, ọrun ni ọmọ olórin..
wikipedia
yo
Yorùbá máa ń sọ wí pé iṣẹ́ Ọlọ́run tóbi tàbí àwámár ní ìṣe Olódùmarè..
wikipedia
yo
Ọ̀rúnmìlà ló fẹ̀yìntì, ó wò títítítí ó ní ẹ̀yìn ẹ̀rọ okùn, èrò ọ̀sà ń jẹ́ ẹyin ó mọ̀ wí pé iṣẹ́ Elédùmarè tóbi..
wikipedia
yo
Olódùmarè gẹ́gẹ́ bí alágbàára láyé àti lọ́run a dùn ń ṣe bí ohun tí Elédùmarè lọ́wọ́ sí a sọ̀rọ̀ ṣe bí ohun tí Elédùmarè kọ lọ́wọ́ sí, a lèwí lẹ́sẹ̀, aṣekanMakú, ohun tí Yorùbá rò nípa Elédùmarè ni wí pé kò sí nǹkan tí kò le ṣe àti wí pé ohunkíhùn tí ó bá lówó sí ó di dandan kí ó jẹ́ àṣeyọrí àti àṣeyege..
wikipedia
yo
Ní ọ̀nà míràn Yorùbá tún gbàgbọ́ wí pé Ọlọ́run nìkan ni ó gbọ́n, ìdí ni iyì tí Yorùbá fi máa ń ṣọ́ ọmọ wọn ní Ọlọ́rungbọ́n Elédùmarè rí ohun gbogbo, ó sì mọ ohun gbogbo Arínúride, olùmọ̀ràn ọkàn..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ wi pé ojú Ọlọrun ni sánmọ̀ Yorùbá sọ wí pé àmúokun ṣìkà bí Ọba ayé kórí o, Ọba ọ̀run ń wò ó, kí ni ẹ̀ ń ṣe ní kókó tí ojú Ọba ọ̀run kò tó..
wikipedia
yo