cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìpínlẹ̀ ìmọ̀ ìṣègùn lẹ́ni, ní ṣe pẹ̀lú ẹ̀ka ìmọ̀ ìṣègùn, ìwádìí ìṣègùn àti egbògi oníṣègùn, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìwádìí yìí, ìpèníjà ti dé bá àìsàn àti ìpalára.Ìtàn nípa ìmọ̀ ìṣègùn àwọn àpẹrẹ tàbí àwòrán nínú ìṣègùn nií àwọn ìlú púpọ̀ ti ńlo àdánidá orísun bí ohun eléwé tútù (lílò egbògi), ìpín ẹranko àti àwọn nǹkan tí ó wà nínú erùpẹ̀ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ní gbogbo ìlú ìwọ̀-oòrùn, ìmọ̀ wáá lórí ẹṣin àti uàna ẹṣin níí pa ti ìṣẹ́gun..
wikipedia
yo
Ní àwọn àyíká múràn wọ́n ńlo ìmọ̀ ìṣègùn tí ó tan mọ́ es`in, àṣà ìrírí àti àdánidá oríSon nínú ìmọ̀ ìṣègùn.Àwọn ẹ̀sìn mi gbàgbọ́ pé àwọn òrìṣà ni èmi, nipé èmi wà nínú ohun gbogbo àti wípé gbogbo ènìyàn ló ní agbára ogun àti àfọ̀ṣẹ, èyí ló tún fún wọn ní àgbàálẹ̀ a ti wá ìmọ̀ kún ìmọ̀ ìṣègùn.Ìlú Sréekìí ni ìmọ̀ ìṣègùn ti kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹ̀n ìmọ̀ ìṣègùn jẹ́ ìtẹ̀síwájú tuntun láti dá èyí tí ó pọ̀jù lọ nínú ìmọ̀ ìṣègùn nípa ìlò ìlànà ìmọ̀ àti ìṣàjọ́ àwọn ẹ̀rí pẹ̀lú ìdàgbàsókè àwọn ọ̀págun èyí tí ó fọ́nká sí àwọn olùtọ́ ju aláìsàn.Ìlò ìmọ̀ ìṣègùnèyí ni ìmọ̀ bí ẹni ìpìlẹ̀ àti ọ̀nà tí a ń gbà lo àwọn ìmọ̀ ìṣègùn yìí ní àkójọpọ̀..
wikipedia
yo
pẹlu ọgbọ́n inú ati ìdájọ́ ilé-ìwòsàn láti fi mọ ìwòsàn tí ó tọ́..
wikipedia
yo
Àgbède sí ìmọ̀ ìṣègùn ni dókítà aláìsàn jẹ́, onímọ̀ ìṣègùn yìí gbọ́dọ̀ ní ìbátan pẹ̀lú ènìyàn tí ó ní àìsàn láti fi ràn lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àwọn oníwòsàn mìíràn náà ma ń dá àjọṣepọ̀ sílẹ̀ láàrín àwọn àti ẹni tí wọ́n ń tọ́jú láti fi mọ wan dada.Ìwúlò ìmọ̀ ìṣègunláti ṣe ìwádìí àìsàn fún ìtọ́jú àti ìlòsí fún àwọn aláìsàn láti mọ ohun tí ó ń fa àìsàn fún ìmọ̀ nípa lílo àwọn ogun láti dín iye àwọn tí wọ́n ń ṣe àìsàn kù.Ìparí nǹkan tí ó bá ti wà fún ìtọ́jú àìsàn yààlà ni mímú, lílò, fi para tàbí fi sùn, ni à ń pè ní oògùn..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ ìgun jẹ́ ẹ̀ka ìmọ̀ tí ó ń ṣe ìgbìmọ̀ ìtọ́, ìwà àti àfihàn ohun tí ó ń fa àìsàn àti ìtọ́pọ̀ rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ọba Kambodia, tó jẹ́ mimo bí Kampùcheá tẹ́lẹ̀, tàbí , tó wá láti Sankọjá Kaká), jẹ́ orílẹ̀-èdè ní gúúsùila àsìá tó ní bodè mọ́ Thailand ní ìwọ̀òrùn àti àríwáiwoorun, Laos ní àríwá, Vietnam ní ilaorun àti gúúsùilaọrun, àti ìkún-omi Thalá ní gúúsù..
wikipedia
yo
Phnom Penh ni oluilu re ati ilu titobijulọ nibẹ, ohun si tun ni gbanga fun Okòwò, aje, ile-iṣẹ ati asa ni Kambodia..
wikipedia
yo
Siem reap, tó jẹ́ ìlú tó súnmọ́ Angst Wat ní ẹnu bodè sí agbègbè Angst níbi tó jẹ́ ibi ìbẹ̀wò..
wikipedia
yo
Celibang, ilu títóbijulo ni apaiwoorun Kambodia, Ggbajumo fun ogbin iresi re, Sikíákíákville, ilu lẹba odo ni ebute alakoko ati ibi igbadun eti odo.Ìtóbi kambodia fe to ati iye awon eniyan to ju ẹgbẹgbẹ̀rún 14 lo ti won je Khmer..
wikipedia
yo
Aráàlú Kambodia là ń pè ní “Ara Kambomboakdia tabi “Khd", botilẹjẹpe yi to gbeyin yi ntọ́kasí si awon ẹya eniyan Khmer..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn ará Kambodia ni wọ́n jẹ́ ẹlẹ́sìn theravàdá Buddhist, ṣùgbọ́n bakanna ni àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí Cham tún wà níbẹ̀, bákannã àwọn ni àwaon ẹ̀yà Ṣáínà, Vietnam àti àwọn ẹ̀yà ẹlẹ́sìn òòṣà tún wá..Iṣẹ́-àgbẹ̀ ni èyí tó ṣe kókójùlọ nínú okòwò Kambodia, pẹ̀lú bí 59% àwọn ènìyàn ngbéra le iṣẹ́ àgbẹ̀ fún igbe wọn (nibi ti ìrẹsì ti jẹ́ ọ̀gbìn pàtàkì)..
wikipedia
yo
Aṣọ, Isebẹ̀wò, atí ilé kíkọ́ nã tún ṣe pàtàkì, ìbẹ̀wò àwọn ara òkèrè sí Angst Wat fẹ́ tó ẹgbẹgbẹ̀rún 4..
wikipedia
yo
Ni 2005, yíe ilẹ̀ bi epo ati ẹ̀fúùfù àdánidá jẹ́ wiwari ni lábẹ́ agbègbè omi Kambodia, nígbàtí wiwajade wọn fun tita ba bẹrẹ ni 2011, ipawo epo yi yio kópa gidigidi lori oko ilẹ̀ Kamboak.itọkasi..
wikipedia
yo
Ó ní bodè mọ́ India ní gbogbo àwọn ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ àyàfi fún bodè kékeré mo Burma (Myanmar) ní gúúsùìlà àti mọ́ ẹ̀bádò Bengal ní gúúsù..
wikipedia
yo
Lápapọ̀ mọ́ ìpínlẹ̀ West Bengal ní India, ó jẹ́ agbègbè ẹ̀yà-èdè Bengal..
wikipedia
yo
Orúkọ Bangladesh túmọ̀sí “orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Bengal” ní èdè ibiṣẹ́ Bengal.Àwọn bodè Bangladesh lọ́wọ́lọ́wọ́ ló jẹ́ ìṣẹ́jú pẹ̀lú ìpinyà Bengal àti India ní 1947, nígbàtí agbègbè nà di ẹ̀gbẹ́ apáìlà orílẹ̀-èdè tuntun Pakistan..
wikipedia
yo
ṣùgbọ́n, ó pínsọ́tọ̀ láti ẹ̀gbẹ́ apáìwọ̀run pẹ̀lú ilẹ̀ Íńdíà..
wikipedia
yo
Nítorí ìdáwàlo olóṣèlú àti èdè àti àìsí okòwò tó fa ìsọdi àwọn aráàlú sí ìwọ̀òrùn Pakistan, tó fa ogun fún ìlòlọ́mọ ní 1971 àti ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè Bangladesh..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìlòlọ́mọ orílẹ̀-èdè tuntun yí kojú ìyàn, àjálù ẹ̀dá àti àìní tógbálẹ̀, àti wàhálà òṣèlú àti ìgbàjọba ológun..
wikipedia
yo
Epada oseluaráàlú ni 1991 mu Ìtọrọ àti ìdàgbàsókè okowo wá.Bangladesh ní Orílẹ̀-èdè Keje tó lọpọ̀ ènìyàn jùlọ àti ìkan nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó lọ́pọ̀ ènìyàn kìkìjùlọ láyé pẹ̀lú òṣùwọ̀n àìní gíga.Síbẹ̀síbẹ̀, Gd ti ẹnìkọ̀ọ̀kan ti di ẹ̀mejì láti 1975, bẹ́ síni òṣùwọ̀n àìní tí rẹ̀ bí 20% láti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1990..
wikipedia
yo
BANGLADESH jẹ́ ìkan nínú àwọn orílẹ̀-èdè tí à npè ní okòwò “Next Eleven”
wikipedia
yo
Dhaka, oluilu rẹ̀, àti àwọn gbọ̀ngàn ìgboro ìlú míràn kópa nínú ìdàgbàsókè yí.Fún Jeografi, orílẹ̀-èdè yí gba ilẹ̀ ọlọ́rà Delta Ganges-Brahmaputra bẹ̀ síni òun ni ọmọyalé lododun ọjọ́ monsoon àti ìjì bìrìkìtì..
wikipedia
yo
BANGLADESH ní ilẹ̀ yẹ̀pẹ̀ etí-odò tó ẹ̀wùẹ́ láyé ní ti Cox's Bazté):
wikipedia
yo
BANGLADESH jẹ́ ìkan nínú àjọni àwọn orílẹ̀-èdè, ọ̀pọ̀lọ́, sáàjókòó, papọ̀ste, àti d-8..8..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Báńkì Àgbáyé ṣe ṣàkíyèsí nínú ọ̀rọ̀ nísó orílẹ̀-èdè rẹ̀ ní July 2005, Bangladesh ti ní ìlòsíwá gidi ní ìdàgbàsókè ènìyàn ní apá ìmọ̀okomọ̀ọ́ká, ìdọ́gba akọ/abo ní ilé-ẹ̀kọ́ àti ìrẹ̀sílẹ̀ ìpọ́jú àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
However, Bangladesh sì nkọju awọn iṣoro nla, ajakale ìwaibàjẹ́ àwọn oloselu ati oṣiṣẹ ijọba, Economic competition Láwọnte to the World, Serious Overpopulation, Ìpolongogi Poverty, and an Àpapọ̀ Danger of hydrologic Shocks brought on by Ecological vulonly to Clímate Change.Ìtàn àwọn ìṣekú Asaọ̀làjú ní agbègbè Bengal lọsẹ́yìn dé ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ọdún, nígbàtí ibẹ̀ jẹ́ títẹ̀do lọ́wọ́ àwọn Draìmòyeanan, tibẹ̀-toman, àti àwọn Austro-ásìati
wikipedia
yo
Orísun ọ̀rọ̀ Bangla" tàbí "Bengal" Kò jẹ́ mímọ̀, àtìtilẹ̀jẹ́pé wọ́n nígbàgbọ́ pé ó wá láti Bang’’, ẹ̀yà tó ń sédè Draṣíṣàṣàròan to bùdó sí agbègbè yí lãrín ọdún 1000 K€.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Portugal ( ), Loníbiṣẹ́ bi orileominira Portugal (), je orile-ede to bùdó si apagúúsùiwoorun Europe lori penisúlà Iberia..
wikipedia
yo
Portugal ni orile-ede to sunmọ apa iwoorun julo ni Europe, bẹ Sini o ni Bode mo Okun Atlantiki ni iwoorun ati ni guusu, Bode mo Spain ni ariwa ati ilaọrun..
wikipedia
yo
Awọn iṣujo erekuṣu inu Atlantiki, yun Azores ati Madeira jẹ ara Portugal..
wikipedia
yo
Nígbà Reconquis àwọn ẹlẹ́sìn Krístì, Portugal sẹ̀dá ara rẹ̀ bí Ilẹ̀ọba alómìniralómìnira, torí ni wọ́n ṣe unpé bí orílẹ̀-èdè-àjọ-bá tógbọ́jùlọ ní Europe.Ní OrúdNun 15K àti 16K, Ntórípe ó léwájú ìgbà ìriri, Portugal di ilélúkó tó nílẹ̀ kãkiri Áfríkà, àsìá, Oséíà, àti Gúsù Amẹ́ríkà, láti di ìkan nínú àwọn alágbára itokọ́wọ́, olóṣèlú àti ológun lágbàyé..
wikipedia
yo
IleỌbalúaye Portugal ni iledídúróaye Akáríayé akoko ninu itan, ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon Ọbalúaye Alamusìn Europe..
wikipedia
yo
Síbẹ̀síbẹ̀, ipò orílẹ̀-èdè ti jẹ́ kò gan títí tó fi di ìlú 19K, Àgàgà lẹ́yìn ìlọ́mọlọ́mọ ilẹ̀ Brasil, tó jẹ́ imusin tótóbijùlọ rẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí Portu orílẹ̀-èdè elédè eléánù..
wikipedia
yo
JÀMÁÍKÀ ẹ̀ṣẹ́ka jẹ́ orílẹ̀-èdè erékùṣù ní Antilles gbangba, tó jẹ́ ní gígùn àti bí ní fífẹ̀, tí ìsọdipúpọ̀ wọ́n jẹ́ 11,100 km..
wikipedia
yo
O bùdó sínú òkun KariHana, bí gúúsù Kuba, àti ìwọ̀òrùn Hispaniola, erékùṣù tó jẹ́ ilẹ̀ fún àwọn orílẹ̀-ilẹ̀ Haiti àti orílẹ̀-èdè olómìnira Dominikí..
wikipedia
yo
Àwọn elédè arawak abinibi ẹ̀yà Δ tí wọ́n gbé níbẹ̀ pe orúkọ erékùṣù ọ̀hún ní XayMacaroni, tó túmọ̀sí "Ilẹ̀ igi àti omi", tàbí "Ilẹ̀ Ìsun Omi"
wikipedia
yo
Nígbà kan bí Ini Spéì́ì tí wọ́n sì pe ibẹ̀ ní , ni 1655 ó di Ibiàmúsìn Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, àti lẹ́yìn èyí ó di ti Britani, tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “Jamaica..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí wọ́n tó ẹgbẹgbẹ̀rún 2.8, ó jẹ́ orílẹ̀-èdè kẹta elédèGẹ̀ẹ́sì tó ni àwọn ènìyàn pípò ní orílẹ̀ Amẹ́ríkà, lẹ́yìn àwọn orílẹ̀-èdè Ìparapọ̀ Àwọn Ìpínlẹ̀ àti Kánádà..
wikipedia
yo
O wa ninu ile àjọni pẹlu Queen Elizabeth II bi olori orilẹ-ede..
wikipedia
yo
Kingston ní ìlú títóbijùlọ àti olúìlú rẹ̀.Ìtàn àwọn ẹ̀yà abí arawaK àti Rílú tí wọ́n gbéra láti gúúsù Amẹ́ríkà bùdó sórí erékùṣù ná lãrín ọdún 4000 àti 1000 Kj..
wikipedia
yo
NígbàtíChristopher Columbus dé bẹ̀ ní 1494 ó bá àwọn abúlé tó ju 200 lọ níbẹ̀ tí wọ́n ní àwọn olórí abúlé níbẹ̀..
wikipedia
yo
Bédò gúúsù Jàmáíkà jẹ́ ibi tí àwọn ènìyàn Posijùlọ nítọ̀, àgàgà layika agbègbè tí a mọ̀ loni bí Old Harke..
wikipedia
yo
Awọn Cheos si jẹ Oníbúgbe Jàmáíkà nigbati awọn Gẹẹsi gba idari ibẹ̀..
wikipedia
yo
Jamaican National Heritage trust nṣiṣẹ lati wárí, ki won o si ṣàkọsílẹ̀ ẹri yiowu tọba le wa nipa awọn Δ/arawaks..
wikipedia
yo
Christopher Columbus gba Jamaica fún Speińì lẹ́yìn tó balẹ̀ síbẹ̀ ní 1494..
wikipedia
yo
Ó ṣe é ṣe kó jẹ́ pé ibi tí Columbus balẹ̀ sí ni dry harBour, loni tó ń jẹ́ Discovery Bay..
wikipedia
yo
Ann’s Bay ní ibi ibùdó àkọ́kọ́ àwọn ará Spéìn lórí erékùṣù nã, Ṣẹ́Villa, tí wọ́n pati ní palọ́wọ́ nítorí ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́ṣà tí wọ́n já bẹ̀.Wọ́n kó olúìlú ibẹ̀ lọ sí Spanish Town, lọ́ni tó bùdó sí Elih of St..
wikipedia
yo
Spanish Town ni o ni Ile Ìsìn to peJùlọ lãrín àwọn Ibiàmúsìn Britani..
wikipedia
yo
Àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì fi tipátipá lé àwọn ará Spéìsí kúrò ní òcho Rios ní St..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, ó di ọdún 1655, ní Tower Isle, kí àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ó tó gba ọgbà ológun àwọn ará Spéìn tó gbẹ̀yìn ní Jamaica..
wikipedia
yo
Ọmọ Spepéì tó ń jẹ́ Don Corte Arnoldo dé Yssi dá abọ́ bo àwọ Hill (Ibi tí Tower Isle wà) lọ́wọ́ àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì fún ọdún márùn, kí ó tó gbé sí Kuba..
wikipedia
yo
Ibi tó gbà sálọ ni wọ́n ń pè ní “Run Bay”, èyí na wá ní St..
wikipedia
yo
James, wá láti orúkọ lédè Spéìn (tàbí Bay of Lard) fún ọ̀pọ̀ iye púpọ̀ Arired tí wọ́n ń lọ fún Lard-Making Industry.
wikipedia
yo
And Privateer Who Had arrived in the West Indies as an indenwọnú servant, like many of the early settlers.Ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì Admiralral William Penn (baba William Penn ti Pennsylvania) ati ọ̀gágun Robert Venables gba Erékùṣù yi ni 1655..
wikipedia
yo
Ni 1660, iye àwọn ènìyàn ní Jàmáíkà jẹ́ 4,500 àwọn aláwọ̀ funfun àti bí 1,500 melo àwọn aláwọ̀ dúdú..
wikipedia
yo
Lati bi àwọn ọdun 1670, àwọn èniyàn aláwọ̀ dúdú ni wọ́n jẹ́ ogúnlọ́gọ̀ iye àwọn ènìyàn nibẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì gbà Jamáíkà ní 1655 Olùmúsin ará Spéìsí sá kúrò níbẹ̀ wọ́n sì fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ ẹrù wọn láti Áfríkà sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ki àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ó mo báa tún mú wọn lẹ́rú, wọ́n gbéwẹ́ sí agbègbè òkè Òsùnwí ní orí Erékùṣù yí, níbi tí wọ́n ti darapọ̀ mọ́ àwọn míràn tí àwọn na ti sá kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Spéìsí tẹ́lẹ̀ láti lọ gbé pẹ̀lú àwọn ìjíyẹ́́n..
wikipedia
yo
Àwọn ẹrú tí wọ́n ti sálọ wọ̀nyí jẹ́ mímọ́ bí Jamaican Mameme, kọjá lu àwọn ará Britani ní ọ̀rúndún 18th..
wikipedia
yo
Nígbà ọkọ̀ ẹrù àwọn Mametá ṣedásílẹ̀ àgbájọ alómìnira lãrín inú òkè ilé Jamaica níran dẹran.Nígbà àwọn ọdún 200 àkọ́kọ́ ìjọba Britani, Jàmáíkà di ìkan nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣíwájú lágbà tó ń ta ṣúgà àti tó ń lo ẹrù, nípa ṣíṣe iye tó ju tọ́ọ̀nù 77,000 ṣúgà lọ lọ́dọ́dún lãrín àti 1824 ?”
wikipedia
yo
Leyin ipare owo eru (eyi yato si oko eru gan ti won ko parẹ́) ni 1807, awon ara Britani mu awon ara India ati ara Ṣáínà wa bi awon onifa lati sise..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ-ọmọ awo àwọn oníwó Lwà àsìá yí sí wa ní Jàmáíkà títí dòní.Nígbà tó fi di ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún 19th, nítorípé Jamaica gbọ́kàn lé oko ẹrú èyí kí àwọn ènìyàn Aláwọ̀dúdú (àwọn ará Áfríkà) ó pọ̀ju àwọn ènìyàn aláwọ̀funfun (àwọn ará Europe) lọ ní ìpín 20 sí 1..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé àwọn Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ti fi òfindé ọwọ́ ẹrú, ìfàyàwó wọn si àwọn Ibiàmúsìn sì tún ṣẹlẹ̀ nígbànã..
wikipedia
yo
Ìjọba Britani ṣe òfin tó lànà iparẹ̀ oko ẹrú, ṣùgbọ́n wọ́n tún lànà láti ṣe imudara igbe àwọn ẹrú ibẹ̀..
wikipedia
yo
Ninu awọn ìlànu yi ni ìfòfindè lilo Egba ninu oko, ìfòfindè níná awon obinrin, ikede pe awọn ẹru gbọdọ jẹ gbigba laye lati gba ilana esin, ipọndandan pe awọn ẹru gbọdọ ni ọjọ kan ninu ose lati ta awọn ogbin ọkọ wọn, bakanna wọn si tun durode awọn ọja ọjọ Aiku.Ṣugbọn ni Jàmáíkà, awọn ilana yi jẹ lílòdì di latọwọ ile-igbimọ aṣofin..
wikipedia
yo
Ileigbimo yi so pe awon ẹru nitẹ ara won, won si lodi si itọwo ileasofin si oro to n lo ni Erekusu ohun, botilẹjẹpe opo awon to ni eru n bẹru pe Jẹdìde awon ẹru le se.leyin opolopo àìgbọràn ati iyipada iwuwa ni Britani olokiki, won duro oko ẹru ni 1834, pelu ifisile patapata lowo idẹkùn ẹru ni 1838..
wikipedia
yo
Iye àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni 1834 jẹ́ pań,070 nínú àwọn ti 15,000 jẹ́ aláwọ̀funfun, 5,000 jẹ́ ènìyàn Aláwọdúdú alómìnira, 40,000 ẹ̀yà àdàlú, àti herodioni,070 ẹrú.Ní àwọn ọdún 1800, Britani ṣẹ̀dásílẹ̀ iye àwọn ọgbà ewéko..
wikipedia
yo
Ìkan nínú wọn ní Castleton garden, tó jẹ́ dídakalẹ̀ ní 1862 láti dípò Bath garden (tó jẹ́ dídà ní 1779) tí àgbàrá omi bàjẹ́..
wikipedia
yo
Bath garden ní ibi ọ̀gbìn Breadfruit tí wọ́n jẹ́ mímúwa sí Jamaica láti Pacific látọwọ́ Captain William bligh..
wikipedia
yo
Awon ogba miran tun ni akọ́rọ́ Plantation ti won dasilẹ ni Ibra ati Hope GARl ti won dasilẹ ni 1874..
wikipedia
yo
Ní 1872, Kingston di oluilu erékùṣù na.Ní 1945, sir Horace Héctor Hearne di onídàjọ́ àgbà àti olùtọ́jú àkọsílẹ̀ ní Jàmáíkà..
wikipedia
yo
O ṣolori ile-ẹjọ gigajulọ, Kingston larin 1945 ati 1950/1951..
wikipedia
yo
Ibe lo gba lo si Kenya nibi ti won ti yan bi onidajọ agba.Díẹ̀díẹ̀ Jàmáíkà gba Olatàbi lopo lowo Ìparapọ̀ Ilẹ̀ọba Be Sínì ní 1958, ó di igberiko nínú Federation of the West Indies, Ilé àapapọ̀ kan ní larin àwọn British West Indies..
wikipedia
yo
JÀMÁÍKÀ gba iòmìnira pátápátá nígbà tó fi ilẹ̀ àpapọ̀ yí sílẹ̀ ní 1962.Okòwò tó ń pósí daada bí 6% lọ́dọọdún, ló ṣẹlẹ̀ ní ọdún mẹ́wá àkọ́kọ́ lẹ́yìn Ìlọ́mọlọ́mọ lábẹ́ ìjọba tí àwọn alákóso àgbàálẹ̀ Bustastatenò, Donald Sanzenhausen àti Hugh Sheli solo rí sírere..
wikipedia
yo
Ohun to fa igege yi ni inawolori daada si omi/alumina, Iṣẹbẹ̀wò, ile-iṣẹ elero ati, ni bi die apa iṣe agbe.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Thierry Henry jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ọmọ ilẹ̀ Fránsì.Ìtọ́kasí àwọn ará Fráǹsì..
wikipedia
yo
Muhammad Ali (Orúkọ àbísọ Cassius Marlus Clay, Jr.; January 17, 1942 – June 3, 2016) jẹ́ ajẹ́ṣẹ́ ará Amẹ́ríkà tó ti fẹ̀yìntì àti onídárayá àkọ́kọ́ àgbáyé fún wúwotowúwo ní ẹ̀ẹ̀mẹta.A bí Ali sí Louisville, Kentucky òsì dàgbà sì bẹ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ni ọdun 18, o ṣẹgun goolu kan ni pipin iwuwo iwuwo ina ni awọn Olimpiiki Igba Adanu Ewe 1960 ati pe o di alamọdaju nigbamii ni ọdun yẹn..
wikipedia
yo
O bori ni aṣaju iwuwo iwuwo agbaye lati ọdọ Sonny Liston ni ibinu nla ni ọjọ kinni 25, 1964, ni ọjọ -ori 22..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹta ọjọ́ 6, 1964, ó kéde pé òun kò ní mọ́ mọ́ Cassius clay ṣùgbọ́n bí Muhammad Ali..
wikipedia
yo
Ní 1966, Ali kò láti jẹ́ kí ó wá sínú ológun, ní sísọ àwọn ìgbàgbọ́ ẹ̀sìn rẹ àti àtakò ìhùwà sí ogún Vietnam..
wikipedia
yo
O jẹ̀bi pe o yàgò fun kikọ silẹ nitorina o dojukọ ọdun marun ninu túbú ati pe o gba awọn akọle Boxing rẹ..
wikipedia
yo
O duro kuro ninu tubu bi o ti bebe fun ipinnu si ile -ẹjọ Adajọ, eyiti o yi idajọ rẹ pada ni ọdun 1971, ṣugbọn ko ti ja fun ọ fẹrẹ to ọdun mẹrin o padanu akọkọ iṣẹ ṣiṣe giga bi elere idaraya..
wikipedia
yo
Awon ise Ali gege bi alatako-okan si ogun Vietnam je ki o je aami fun iran counterculture ti o tobi, ati pe o je eeyan ti o ga pupo ti igberaga elẹ́yàmẹyà fun awon ara Amerika Amerika lakoko gbigbe awon eto ara ilu ati jakejado iṣẹ rẹ..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Musulumi, Ali ni ajọṣepọ lakoko pẹlu Elijah Muhammad's Nation of Islam (Tgaines)..
wikipedia
yo
Nigba o kọwọ si noi, ti o faramọ Islam Sni, ati atilẹyin isoji ẹya bi Onimọran iṣaaju rẹ Malcolm X..
wikipedia
yo
O kopa ninu ọpọlọpọ awọn ere -idije Boxing ni pataki julọ awọn ija rẹ pẹlu Joe fRaza] pẹlu ija ti ọdun (iṣẹlẹ afẹṣẹja ti o tobi julọ titi di igba naa), Thrillarilla ni Manila, ati ija rẹ pẹlu George forforeman ti a mọ si The Rumble ninu Jung, eyiti o jẹ wiwo nipasẹ igbasilẹ ti a fojusi awọn olugbohunsafefe tẹlifisiọnu ti awọn oluwo bilionu 1 ni kariaye, di igbohunsafefe tẹlifisiọnu laaye julọ julọ ni agbaye ni akoko yẹn..
wikipedia
yo
Ali ṣe rere ni ìrànrán ni akoko kan nigbati ọpọlọpọ àwọn oníjà jẹ ki àwọn alakoso wọn soro, ati pe o jẹ igbagbogbo ni ìmúnibínú ati ajeji..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olókìkí fún sísọ ọ̀rọ̀ ìdọ̀tí, àti ìgbàgbogbo ní asà-ara pẹ̀lú àwọn ètò orin àti ọ̀rọ̀ ewì ọ̀rọ̀, ìfojúsọ́nà àwọn èròjà ti hip hop..
wikipedia
yo
ní òde òrùka, Ali ti ṣaṣeyọri bi oṣere olórin ọ̀rọ̀, nibiti o ti gba àwọn yiyan Grammy meji..
wikipedia
yo
O tun ṣe ifihan bi oṣere ati onkọwe, dasilẹ awọn itan -akọọlẹ ara ẹni meji..
wikipedia
yo
Ali ti fẹyìntì lati afẹṣẹja ni ọdun 1981 ati idojukọ lori ẹsin, alãnú ati ijagbara..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1984, ó ṣe àgbékalẹ̀ ìwádìí àìsàn ti Parkinson's syndrome, èyítí díẹ̀ nínu àwọn ijabọ ṣe ìkàwé sí àwọn ipalara tí ó ní ìbátan Boxing, bótilẹ̀jẹ́pé oun àti àwọn ìgbòó alamọja rẹ̀ tako eyi..
wikipedia
yo
O jẹ eniyan ti n ṣiṣẹ lọwọ ni kariaye, ṣugbọn ni awọn ọdun igbẹhin rẹ ṣe awọn ifarahan gbangba diẹ bi ipo rẹ ti buru si, ati pe idile rẹ tọju rẹ..
wikipedia
yo
Ali ku ni osu karun ojo 3, odun 2016.Awon itọkasiÀyọkà kukuruawon to gba eso Wúrà látinú fun orile-ede Ameriìyọnuwon omo Afrika Ameriìyọnuwon ajese ara Amerika..
wikipedia
yo
Kogọlọ́yàyà (), fún Orioris bi orílẹ̀-èdè òtòsí ilé Kolò (, ), jẹ́ orílẹ̀-èdè òtòsí òdì-ẹ̀wà ní arít gúúsù Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Kolopajú ní Bode ní Ilaorun pèlú Venezuela ati Brazil; ní gúúsù pẹ̀lú Ecuador àti Peru; ní àríwá pẹ̀lú òkun KariZulu; ní àríwáilaorun pẹ̀lú Panama; àti ní ìwọ̀òrùn pẹ̀lú okùn pàsífìkí..
wikipedia
yo