cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Adolf báPọ́ńtíù, láti Yunifásítì ìlú Berlin, Mugbajúmọ̀ pẹ̀lú ìwé rẹ̀ Indoenen Oder die Kídun des Malayichen 1731Ará] 1884-1894..
wikipedia
yo
Olukọwe ara INDONESIA to kọkọ lo orukọ yi ni Suwardi Suryaning (Ki Hjar Dewantara), nigbato da iso akéde sile ni RSanlándi pẹlu orukọ Indonech pers-Bureau ni 1913itọkasi.
wikipedia
yo
James Arthur baldwin (August 2, 1924 – December 1, 1987) jẹ́ ara Amẹ́ríkà àròtanko, Olùkọ̀wé, Aroko, akọewi, aláròkọ àti alákitiyan àwọn ètò aráàlú.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1924àwọn Ojoaláìsí ní 1987Àwọn Olukọwe ara Américo ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Oloye Daniel Orowole OlorunFemi Fágúnwà mbẹ (1903 – 7 December 1963), ti gbogbo eniyan mo si D..
wikipedia
yo
Fágúnwà, ó jẹ́ ògúná gbòngbò ti dá ìtàn àròsọ ni èdè Yorùbá sílẹ̀, àti olùkọ́ èdè Yorùbá nígbà ayé rẹ̀..Ìgbé ayé rẹ̀wọn bí Fágúnwà ni ilú Òkè-igbó, ni ìpínlẹ̀ Òǹdó..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ ni ọ̀gbẹ́ni Joshua Akíntúnde Fágúnwà nígbà tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Rachel Osun Fágúnwà..
wikipedia
yo
Bàbá Bàbá rẹ̀ ní Fáníyì Újò, tí Ò jẹ jagun-jagun..
wikipedia
yo
Ọmọ ọmọ fa ní yí yí ni Erusola àsùngágá jìnòkú, tí ó jẹ adífálà ní ìlú orígbọ́, ìlú tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ìlú Ipetumodu..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìyá ìyá rẹ̀ ń jẹ́ sáyọ̀ade Olowu, tí ó jẹ́ ọkàn nínú ọmọ bíbí Owu ṣẹ kí wọ́n ti gbéra lọ sí ìlú Abeokuta..
wikipedia
yo
àsùngágá yi ni ó kó lọ si ìlú Ilé-Ifẹ̀ látàrí bí Àbíkú, bi ó tilẹ̀ jẹ́ wípé òun gan gan fúnra rẹ naa jẹ́ Àbíkú ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ìlú ilé-Ifẹ̀ ní ààrin ọdún 1870,ó di oníṣẹ́gu ati babaláwo fún ọba Ọọ̀ni ti ilé-Ifẹ̀ ologbenlánlá..
wikipedia
yo
KẸ́YÌN ti OGUN ÌFẸ́ ÀTI Oǹdó PARÍ, PÚPỌ̀ NÍNÚ ÀWỌN jagun-jagun ni wọ́n pàgọ́ sí abúlé kan TÍ WỌ́N Ń PÈ NÍ “ỌKỌ̀-IGBÓ” TÍ Ó DI ÒKÈ-I FẸ̀TÍÍ..
wikipedia
yo
àsùngágá bí ọmọ padà bí ọmọ mẹ́rin tí wọ́n gbẹ̀yìn rẹ̀..
wikipedia
yo
Orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Orowole tí ó sì yí orúkọ rẹ̀ padà sí OlaỌ̀runlá nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ yí sí ẹ̀sìn pẹ̀lú
wikipedia
yo
Oun nikan ni ọmọ okurin ti to keyin awon obi re pelu obinrin meta.eto eko re Fágúnwà keko ni ile-eko St..
wikipedia
yo
Andrew's College, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ṣáájú kí ó tó di olùkọ́.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oníoweFágúnwà kópa nínú ìdíje tí Ministry of Education gbé kalẹ̀ ní ọdún 1938, Ìdíje yí ni ó fàá tí ó fi kọ ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere ògbójú ọdẹ nínú Igbó Irúnmọ́lẹ̀, ..
wikipedia
yo
Ìwé yí ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òun ni ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere àkókò tí wọ́n kọ́kọ́ kọ ní èdè Yorùbá , àti ìwé ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere ánọkọ ní èdè ilẹ̀ adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀dá ìtàn inú ìwé rẹ̀ ma ń sábà jẹ́ ọ̀dẹ̀ ni ó ma ń ṣàfihàn wọn bí wọ́n ṣe ma ń bá àwọn irúmọ́lẹ̀ sọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé rẹ̀ tún ṣe ìyàtọ̀ láàrín ẹ̀sìn ìbílẹ̀ àti ẹ̀sìn Kristẹni ti àwọn Gẹ̀ẹ́sì amúnisìn mú wọ ilẹ̀ adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé Fágúnwà ni àwọn ìwé ìtàn àròsọ tí ó gbajúmọ̀ tí àwọn ènìyàn sì ń kà jùlọ, tí iṣẹ́ rẹ̀ ò sì tún jẹ́ ìwúrí fún àwọn òǹkọ̀wé bíi Amos Tutùọlá.Fágúnwà tún lo ọgbọ́n ìsọ̀tàn Shakespeare nínú ìwé rẹ̀ tí ó pè anole rẹ̀ ní Igbó Olódùmarè, níbi tí ó ti lo bàbá onírungbo-yẹ́úkẹ́ láti sọ ìtàn tí ó jọ mọ́ ìtàn ìwé Romeo and Juliet tí Shakespeare kọ..
wikipedia
yo
Bákan náà ni Fágúnwà tún jẹ́ òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ Yorùbá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò lo ìtàn oyè sọ ìtàn rẹ̀.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀wọ́n fún Fágúnwà ní àmì-ẹ̀yẹ ìdánigbọndínlógójì ti Margaret Wrong Prize í ọdún 1955, bákan náà ni wọ́n tún fún ní àmì-ẹ̀yẹ ti member of the Order of the British Empire (mbe) ní ọdún 1959.Ikú Régúnwà jáde láyé ní ọdún 1963 sínú odò kan nígbà tí ó yọ́ ṣubú sínú omi, tí ó sì gbìyànjú láti wẹ̀ jáde ṣùgbọ́n ọkọ̀ ojú-omi oní pákó kan tún ṣubú dé mọ́lẹ̀ tí kò sì ní agbára láti janpata mọ́ títí ó fi ṣaláìsí.Àwọn ohun ìrántí rẹ̀wọ́n kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ Fágúnwà Memorial High School, wọ́n sì sọ ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Òkè-Igbó ní orúkọ rẹ̀ Fágúnwà Grammar School ní ìrántí rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọmọ rẹ̀ Yejídé Ogundipé náà ṣe aṣojú ìlú rẹ̀ ní Ìjọba ẹ̀ṣẹ̀ kúkú (councir/ fún ilé Olù/Okeigbo..
wikipedia
yo
Fágúnwà Day Ayẹyẹ àjọ̀dún ti wọ́n fi n rántí Fágúnwà tí wọ́n pè ní (Fágúnwà Day) ní àwọn ẹgbẹ́ "Society of Young Nigerian Writers" pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Fágúnwà Literary Society àti ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ oníowe èdè Yorùbá gbé kalẹ̀ láti ma fi gbé àwọn ìwé márun ùn lárugẹ.Àwọn ìwé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa ọnà-èdè Fágúnwàolale, OlaNike..
wikipedia
yo
Fágúnwà (1903 — 9 December, 1963) jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní Òkè-Igbó ní ìpínlẹ̀ Oǹdó..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ògúná gbòngbò òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ, bakanaa ó tún jẹ́ olùkọ́ èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
àwọn ìwé rẹ̀ ọlọ́kan-ò-jọ̀kan ló gún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òǹkọ̀wé ilẹ̀ Yorùbá lónìí ní kẹ́ṣẹ́ ní èyí tí ó mú ìlọsíwájú bá èdè Yorùbá lápapọ̀.Àwọn ìwé tó kọ́ọgbójú òde nínú Igbó Irúnmọ́lẹ̀ (1938)Igbó Olódùmarè (1949)Ìrèké oníbù (1949)Ìrìnkèrindò nínú Igbó Elégbèje (1954)àdìtú Olo’’ (1961)Àwọn ìtọ́kasíàwọn Olùkọ̀wé Ara Nàìjíríààwọn Ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó ń gbé ìlú Ọ̀yọ́ jù ni àwọn ẹ̀yà Yorùbá, Olórí ìlú Ọ̀yọ́ ni ikú bàbá yèyé Aláàfin.~~~Ray OníyaLádélé ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Àwọn sáyẹ́ǹsì àwùjọ are the ìtatẹ of academic scholarship that study society..
wikipedia
yo
"Social Science" Is Commonly used as an Umpertaining term to refer to a plurality of Fields outside of the natural Sciences..
wikipedia
yo
The term may be used, however, in the spenífẹ̀ẹ́ Context of referring to the original Science of Society established in 19th century sociology..
wikipedia
yo
Émile Durkheim, Karl Marx and Max Weber are typically cited as the principal fìdí of Modern Social Science by This Definition..
wikipedia
yo
Posiidì social Scientists use Methods resewo those of the natural Sciences as tools for understanding society, and so define Science in its striìyàlẹ́nu modern sense..
wikipedia
yo
Interpretiidì social Scientists, by contrast, may use social Ọkànmàáque or symbolic ọ̀dọ́odò rather than ócting ipòkípòrically Falfiable the Orò, and thus tÒ science in its first classical sense..
wikipedia
yo
In modern academic practice researchers are often Heberugbára, using multiple methodologies (for instance, by combining the ánantitative and qualitative Techni)..)..
wikipedia
yo
The term "Social Research" has also Acquired a degree of Auto as Practitioners from various disciplines Sha in Its Ams and Methods.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìtàn ni ìgbékalẹ̀ tàbí sísọ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ohun tí ó ti kọjá..
wikipedia
yo
Yoòbá bọ́, wọ́n ní “bọ́mọdé kò bá gbọ́tan, a gbọ́ àrọ́bá... Ìtàn lé wà ní àkọsílẹ̀ tàbí kí o máa ní àkọsílẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn maa n je ki a mo awon isele Meelegbagbe ti o sele nigba ti eniyan ko si laye tabi wa nibi isele naa.Awon itọkasi awon sayensi awujo..
wikipedia
yo
Pages using multiple image with Manual Scaled Imagesọ́sì jẹ́ Ìpínlẹ̀ tàbí ipò nínú èyí tí ènìyàn kò ní àwọn orísun ìnáwó àti àwọn nǹkan pàtàkì fún ìdiwọ̀n ìgbé ayé kan..
wikipedia
yo
O sì lè ní i oríṣiríṣi àwùjọ, àjẹ́, àti òṣèlú okùnfà àti ipá..
wikipedia
yo
ìtumọ̀ ti òṣì ìbátan yàtọ̀ láti orílẹ̀-èdè kan sí ekeji, tabi láti àwùjọ kan sí ekeji..
wikipedia
yo
Awọn ipa awujọ, gẹgẹbi akọ-abo, ailera, ìjẹ ati ẹya, le mu awọn ọran ti osi buru si - pẹlu awọn obirin, awọn ọmọde ati awọn ti o kere julọ nigbagbogbo ti o ńru awọn ẹru aiṣedeede ti osi..
wikipedia
yo
Pẹlupẹlu, awọn eniyan talakà jẹ ipalara diẹ sii si awọn ipa ti awọn ọran awujọ miiran, gẹgẹbi awọn ipa ayika ti ile-iṣẹ tabi awọn ipa ti iyipada oju-ọjọ tabi awọn àjálù adayeba miiran tabi awọn iṣẹlẹ oju ọjọ to buruju ..
wikipedia
yo
Òsì tún lè ṣe àwọn ìṣòro àwùjọ mìíràn burú sí; àwọn títẹ́ ọrọ̀-ajé lórí àwọn agbègbè tálákà nígbàgbogbo ṣe ipa nínú ìpagbórun, ìpàdánù ìpínléríìbò àti ìjà ẹ̀yà ..
wikipedia
yo
Fun idi eyi, awọn ibi-afẹde idagbasoke alagbero ti un ati awọn eto eto imulo kariaye miiran, gẹgẹbi imularada kariaye lati COVID-19, tẹnumọ́ asopọ ti idinku osi pẹlu awọn ibi-afẹde awujọ miiran.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
ìmọnàje (lati inu imo-ede) n dalẹ̀ bi eniyan ati awon eranko se n nilo ati nimo awon irin ati ona ati bi eyi se n nipa lori agbara lati Sedari ati Seapalara mo ibiayika aláàdanida won.itọkasi..
wikipedia
yo
Welele "Ken" Beeson Saro-wiwa (October 10, 1941 – November 10, 1995) je Olùkọ̀wé ọmọ Nàìasetọ́kasí Ọjọ́ìbí ni 1941awon ojoalaisi ni 1995awon ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ọ̀rúndún mìb Ọ̀rúndún 2K Ọ̀rúndún 3 Ọ̀rúndún 4K Ọ̀rúndún 5 Ọ̀rúndún 6K Ọ̀rúndún 7 Ọ̀rúndún _*8 Ọ̀rúndún 9 Ọ̀rúndún 10K Ọ̀rúndún _*11 Ọ̀rúndún _*12 Ọ̀rúndún _*13 Ọ̀rúndún _*14 Ọ̀rúndún 15 Ọ̀rúndún 16 Ọ̀rúndún 17 Ọ̀rúndún _ 18 Ọ̀rúndún 19 Ọ̀rúndún 20 20 Ọ̀rúndún 21 Ọ̀rúndún 22 Ọ̀rúndún 23 Ọ̀rúndún 24 Ọ̀rúndún 25 Ọ̀rúndún 26k Ọ̀rúndún 27 27 Ọ̀rúndún 28 Ọ̀rúndún Ọ̀rúndún 29 Ọ̀rúndún 30 Ìtọ́kasí Àwọn Ọdún Erékùṣù Àsìkò..
wikipedia
yo
Isẹ́ju ìlùlùní ní ó wà nínú wáwá Ìtọ́kasí.àwọn ẹyọ àsìkò..
wikipedia
yo
Owerri ( , ) ní olú-ìlú Ìpínlẹ̀ ìmọ̀ ní Nàìjíríà, ìlú náà wà láàrin ilẹ̀ ògbò..
wikipedia
yo
Oun tun ni ilu ti o tobi ju ni ipinle Imo, ilu Orlu, Okigwe ati Oji/egbema si ni o tele..
wikipedia
yo
Owerri ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́ta, àwọn ní Owerri Municipal, Owerri North àti Owerri West, ìlú Owerri ní àwọn olùgbé 1,401,873 ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Owerri pín alá pẹ̀lú Otamiri River ní apá ìwọ̀ oòrùn rẹ̀ àti Nworie River ní apá Gúúsù rẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí Nàìjíríàoluilu Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n sọ ìlú náà di olú-ìlú ìpínlẹ̀ Anambra ní 21 August 1991, nígbà tí wọ́n ya ìpínlẹ̀ Anambra kúrò lára ìpínlẹ̀ Enugu..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi àbáyọrí ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà, àwọn olùgbé Akwa tó 301,65..7..
wikipedia
yo
Ipinle Awka wa laarin Onitsha ati Enugu.Awon itọkasi oluilu ipinle Naijiria..
wikipedia
yo
Bauchi jẹ́ oluilu ipinle Bauchi ni Naijiriaoluilu ipinle Naijiria..
wikipedia
yo
SARG jẹ́ olúìlú Ìpínlẹ̀ Bàtata ní Nàìjíríà Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Stileyah Dana Haiughton (January 16, 1979 – August 25, 2001), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sì Ètòteyah jẹ́ olórin ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní Brooklyn, ní ìpínlẹ̀ New York, ó sì dàgbà ní Detroit ní ìpínlẹ̀ Mishiganítokasiàwọn Ọjọ́ìbí ní 1979àwọn Ọjọ́aláìsí ní 2001àwọn akọrin ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
A BÍ Thomas Hardy (2 June 1840 - 11 January 1928) ní 1840..
wikipedia
yo
O kò tó ẹgbẹ̀rún ewì irú èyí tí a máa ń pè ní 'Short lyrics *
wikipedia
yo
Ewì rẹ maa ń kún fún òótọ́ o sì máa ń mú ènìyàn lára.Ìtọ́kasí..I..
wikipedia
yo
Williams Butler Yeats (; 13 June 1865-28 January 1939) jẹ́ akéwì àti onímọ̀ nínú lítíréṣọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
O gba pe nǹkan tí ó bá ṣẹlẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún méjì ọdún kan ni yóò tún ṣẹlẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún méjì ọdún tí o bá tún tẹ̀lé e.Ìtọ́kasí yẹats, Williams Butler..
wikipedia
yo
Edwin Muir (15 May 1887 – 3 January, 1959) a bi Muir ní 1887..
wikipedia
yo
Ni 1901 si 1902 ni o tẹle awọn obi rẹ lo si Glasgow..
wikipedia
yo
Kò pé tí wọ́n dé Glasgow ti bí bàbá, ìyá àti àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ méjì kú..
wikipedia
yo
Kò tíì ju ọmọ ọdún mejidinlogun lọ lásìkò yìí káńsà (cancer) ni ó pa ìyá rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ku òun nì, ó bẹ̀rẹ̀ sí nií ṣe iṣẹ́ akọ̀wé ní Glasgow..
wikipedia
yo
Charles Olson (27 December 1910 – 10 January 1970) jẹ́ akọ-ewì ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O wa lara awon ti won mo mo Black Mountain College..
wikipedia
yo
Onkọwe ni o si ti kọ ọpọlọpọ ewi ko ni ifẹ si pe a n ṣapejuwe lo rẹ rẹ rẹ ninu ewi tabi ki a maa lo afiwe taara alooda.Awon ara Amẹrika..
wikipedia
yo
Sylvia plath (October 27, 1932 – February 11, 1963) a bi plath ni ọdun 1933..
wikipedia
yo
Ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni ṣùgbọ́n Jámánì ni àwọn òbí rẹ̀ ti wá..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́sàn-an ó ní 'Shock' nítorí ikú bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú bá ní University ti Bosstonton.[
wikipedia
yo
Gbogbo ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ sí i yìí ni ó ń han nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ewì tí ó kọ..
wikipedia
yo
O fẹ́ akéwì ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Ted Hughes..
wikipedia
yo
A Álvarez ni ó tẹ ìtàn ikú tí ó kú ní rèwerèwe jáde.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Ọdún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wọ́n gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad..
wikipedia
yo
òun ni ó wà ní ipò kẹfa ti a bá ni ki á ka àwọn ilú ti ó tóbi ni ilé-ayé..
wikipedia
yo
USAMKI Cathedral tí ó wà ní ibẹ̀ ni wọ́n ti máa ń dé àwọn tSar (ÀWỌN olùdarí́dárí RỌ́ṢÍÀ) lálá láyé ÀTIJỌ́..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ ati ile-eko po ni ibe lara awon ile-eko ibe ni..
wikipedia
yo
lomonoríbẹ̃ University tí ó jẹ́ University ìjọba wà ní ibẹ̀..
wikipedia
yo
Ori oke Lenin ni won ko o si oun si ni University ti o tobi ju ni Rọ́ṣíà..
wikipedia
yo
Àwọn BolshoI Theatre and Ballet, the State Symphony OCHELtra ati the state folk Dance company tí ó wà ní Moscow gbayì gan-an ní.Ìtọ́kasí àwọn olúìlú ní Europe..
wikipedia
yo
Mozambique, fún ibiṣẹ́ Olómìnira Ilẹ̀ Mozambique ( tàbí RePublica de Moçambique, ), jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apágúila Africa tó ní bodè mọ́ Òkun Íńdíà ní Ilaorun, Tanzania ní Àríwá, Malawi àti Zambia ní Àríwáìwọ̀t, Zimbabwe ní ìwọ̀òrùn àti Swaziland àti Gúúsù Áfríkà ní Gúúsùìwọ̀.abẹ́ Portugal ní Mozambique wà tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tí ó wà ní bèbè Mozambique bíi Laurence Marquis (tí ó jẹ́ olú-ìlú Mozambique) àti Beira ni àwọn ọkọ̀ ojú omi ti ń gúnlẹ̀..
wikipedia
yo
Ọkọ̀ ojú irin ni ó so àwọn ìlú wọ̀nyí mọ́ àwọn ilẹ̀ tí ó kan Mozambique gbangban..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú wọn ni ó ń ṣiṣẹ́ ní South Africa níbi tí wọ́n ti ń wá ohun lọ́dún-ọnnì ilẹ̀ (minerals)..
wikipedia
yo
Àwọn ara Portugal bẹ̀rẹ̀ síí wá sí ibẹ̀ ní nǹkan bí 1500..
wikipedia
yo
Àwọn ilé-iṣẹ́ (companies) ni ó ń darí ilẹ̀ yìí láti 1891 sí 1942..
wikipedia
yo
Ọdún 1942 ni Ìjọba Portugal bẹ̀rẹ̀ síí dari ilẹ̀ yìí..
wikipedia
yo
Ni 1960 ati 1970, Portugal ko ọpọlọpọ ọmọ ogun lọ si Mozambique lati bá àwọn ti o n ja fun ominira ja.itọkasi..
wikipedia
yo
Àwọn ẹfọ̀n burú gan-an ni nítorí pé wọ́n máa ń tan àìsàn ká..
wikipedia
yo
Ẹ̀fọn tí ó bá jẹ́ abo ni ó máa ń fa ẹ̀jẹ̀ ènìyàn tàbí ti ẹranko mu..
wikipedia
yo
Ibi tí ó ti ń fa ẹ̀jẹ̀ mu yìí ni ó ti máa ń tan àìsàn ká..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ kan sí márùn-ún, ẹyin yìí yóò pa yóò di ‘Lare’, eléyìí ni yóò di ‘pupa’ẹ kí ó tó wá di ẹfọ̀n lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta.A lè fín òógùn sí ẹfọ̀n láti pa á tàbí kí a máa jẹ́ kí ó rí omi yẹ sí tàbí kí á máa sin àwọn ẹja kan tí ó máa ń jẹ ẹyin wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Tí a bá fẹ́ sùn, a lè fi àwọn yí bẹ́ẹ̀dì wá pọ̀ kí ẹfọ̀n ma báa rí àyè wọlé láti jẹ wá.Gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀ ṣe fi lọ́lẹ̀, abo ẹfọ̀n ni ó máa ń fa aisan iba lára ènìyàn.Ìtọ́kasí kòkòrò..
wikipedia
yo
Láti nǹkan bí ọmọ ọdún mẹ́ta ni ó ti ní etí inú fún orin..
wikipedia
yo