cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Láìpẹ́ sí ìgbà yìí ni ó ti bẹ̀rẹ̀ sí níí lo ọpọlọpọ irin iṣẹ́ tí wọ́n fi ń kọrin..
wikipedia
yo
Ìlú yìí ni baba rẹ̀ ti ń ṣiṣẹ́ orin kíkọ ní ààfin archbishop ti Salzburg..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdún mẹ́fà ni Mozart nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin gan-an..
wikipedia
yo
Ó bá baba rẹ̀ àti àǹtí rẹ̀ ṣe ìrìnàjò lọ sí ìlú Òyìnbó..
wikipedia
yo
gbogbo eniyan ló ń gbé wọn gẹ̀gẹ̀ ní gbogbo ibi tí wọ́n lọ..
wikipedia
yo
Ìgbà yìí ni Mozart ti bẹ̀rẹ̀ síi kọ orin fún ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ń kọ́ opera, choral music, Orcheélaz music àti Chamber music..
wikipedia
yo
Ara awon opera ti o ko ni 'The Marrce of Figaro' ’Di Giovanni' ati the Magic FluxteMorning
wikipedia
yo
Lara awon Syhónìes bi ogoji ti o ko 'Jupiter' tabi 'Symphony c majorọ̀gágun
wikipedia
yo
'mpmpmp ni g Minor' ati ‘The Symp in e Flat Major' ni ọ̀pọ̀ sọ pe ó dára jù lára iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ mìíràn tí ó lapere ní 'Ẹine Kleine káwarírank8C’ tí ó jẹ́ ‘orinàkóso’ àti ‘Sinẹlẹ́wà rírante' tí ó jẹ́ ‘12to' fún violin àti Viola..
wikipedia
yo
Ọmọ ọdún márùndínloòjìji péré ni nígbà tí ó kú wọ́n sì sin ín sí ibi tí wọ́n máa ń sin àwọn òtòṣì sí ní Vienna.Mozart..
wikipedia
yo
It Duce tí ó dúró fún olórí (The leader) ni àwọn ẹ̀yìn rẹ̀ máa ń pè é..
wikipedia
yo
Setilìni ati Igbimọ FAcist Party ni won jo n dari Italy..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ ajafun-mẹ̀kúnnù (Socialist) ní mussohni ṣe wo ọ̀la..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olóòtú ìwé-ìròyìn kan tí ó ń jẹ́ ní Avanti ṣùgbọ́n ní 1914, ó dá iwe-iroyin tirẹ̀ sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ero ti o ni nipa dida egbe oselu yii sile ni lati le tun Italy ko ki o si so o di ilu ti o lagbara..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí àwọn fáyíncist rìn lọ sí Róòmù ní 1922 (FA’cist March on Rome' Ọba Victor Emmanuel III pe Musnwọn láti wá gbé ìjọba tirẹ̀ kalẹ̀..
wikipedia
yo
Awon omo ogun musÌlérí kọlu ethopia ni 1905 won si Segun ibe leyin opolopo ija ti o gbọ̀nà..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ tí muslìni ní kí àwọn ọmọ ogun òún lọ ran General Franco lọ́wọ́ nínú ogún abẹ́lé ilẹ̀ Spain..
wikipedia
yo
Ní 1940, Italy bẹ̀rẹ̀ síi kópa nínú ogún àgbáyé kejì..
wikipedia
yo
Italy duro gba gba gba ti Germany ṣùgbọn won ṣẹgun Italy..
wikipedia
yo
Àwọn German gbà á sílẹ̀ ó wá di olórí ìjọba tí kò fẹsẹ̀ múlẹ̀ kan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1945, àwọn tí ó ń jà rí í mú, wọ́n sì pa á.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1883àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1945àwọn Alakoso Àgbà Ilẹ̀ Italia..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn, máa ń rin ìrìnàjò afẹ́ lọ sí ìlú yìí..
wikipedia
yo
Wọ́n ní àwọn ẹ̀ṣọ́ wọ́n sì ní àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó ń sọ epo dọ̀tun..
wikipedia
yo
Àwọn Greek ni ó dà Naples sílẹ̀ ṣùgbọ́n ó bọ́ sí abẹ́ àṣẹ Róòmù ní àwàtúrì kẹrin ṣáájú ibi Kírísítì..
wikipedia
yo
O da duro funra rẹ ni sintúrì kejo leyin iku Oluwa wa..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni ó wá di olú-ìlú fún ìjọba SiAly àti Naples..
wikipedia
yo
ÈYÍ NI ORIN TÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ KAN MÁA Ń KỌ NÍGBÀ TÍ WỌ́N BÁ Ń ṢE Ayẹyẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń kó o ti olórí orílẹ̀-èdè mìíràn bá wá bẹ̀ wọ́n wò..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń kọ́ ọ níbi tí àwọn eniyan bá pé jọ sí tabi ibi òṣèlú tó bá ṣe pàtàkì..
wikipedia
yo
Ẹnìkan lè dá a kọ fún gbogbo ènìyàn tàbí kí gbogbo ènìyàn kópa nínú kíkọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ inú orin yìí máa ń yin orílẹ̀-èdè àti àwọn ènìyàn tí ó wà nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
Orin yìí máa ń sábàá sọ àwọn ohun ribiribi tí ilẹ̀ kan ti gbé ṣe..
wikipedia
yo
Bouget de i'Isle ni o ko orin ti ile Faranse ni asiko ogun ni 1792..
wikipedia
yo
Francis Scott key ni ó kọ́ ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní 1814..
wikipedia
yo
A kò mọ́ ẹni tí ó kọ ‘God Save the Queen' ti ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ṣùgbọ́n 1745 ni wọ́n kọ́kọ́ kọ ọ́..
wikipedia
yo
'Àríṣe, o Com."[ots' ni o bere orin orile-ede Naijiria ti a n lo lọwọlọwọ bayii.itọkasi awọn orin-ìyìn..
wikipedia
yo
Pakistan ( tàbí ; ) (.“ Lotọ́ka bí orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ilẹ̀ Pakistan ránka orílẹ̀-èdè kan ní gúúsù àsíá Asia..
wikipedia
yo
Ibe ni ibi oso agbaye akoko ti orile-ede Burkina Faso wa..
wikipedia
yo
arin gbọngan apa Burkina Faso ni opo awon Ilẹ̀ọba mossi, awon to lagbara julọ ninu wọn ni ti Wagadógò (Ouagadougou) ati Yatenga..
wikipedia
yo
Awon Ilẹ̀ọba wonyi je dídádásílẹ̀ ni ibere orundun ìkẹrìndínlógún latọwọ awon ajagun.lati ileàmúsìn de Olanídèupper Voltàbúina Fasoiseluawon agbegbe, igberiko ati ipinapaologun, olopaa ati Gbógunoriileyiya ati Ojúọjọ́okoeyailu-itọkasiji..
wikipedia
yo
Norrr jẹ́ orílẹ̀-èdè ní orílẹ̀ Europe.Ìtọ́kasí Norrori..
wikipedia
yo
Tùnísíà ( or ; ), Loníbiṣẹ́ bí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ará Tùnísíà ( ), ní orílẹ̀-èdè àpaawájúlóló ní Áfríkà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ orílẹ̀-èdè Maghreb kan, bẹ sí ni ó ni bodè mọ́ Algeria ní ìwọ̀òrùn, Libya ní gúúsùila, àti omiÒkun Mediòkúbẹ̀rẹ̀ sí àríwá àti ìlàỌ̀run..
wikipedia
yo
Ààlà rẹ̀ jẹ́ , pẹ̀lú ìdíyelé alábùgbé tó jẹ́ ẹgbẹgbẹ̀rún 10.4..
wikipedia
yo
Orúkọ rẹ̀ wá láti inú orúkọ oluilu rẹ̀ tunis to bùdó sí àríwá-ìlàòrùn.Tùnísíà jẹ́ orílẹ̀-èdè tó kéréjùlọ tó bùdó sí ẹ̀bá òkè Atlas..
wikipedia
yo
gúúsù orílẹ̀-èdè ná jẹ́ kìkì aginjù Sàhárà, pẹ̀lú èyí tó tó jẹ́ kìkì ilẹ̀ ọlọ́rà àti etí Òkun ..
wikipedia
yo
Àwọn méjèjì kó ipa pàtàkì ìgbà àtijọ́, àkókò pẹ̀lú ìlú Carthage àwọn Punic, lẹ́yìn rẹ̀ bí ìgbèríko ilẹ̀ Romu ní Africa, tó gbajúmọ̀ bí “Àpẹrẹ onjẹ /Bread Basket ilẹ̀ Romu..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn rẹ̀, Tùnísíà bó sọ wọ àwọn Vandals ní ọ̀rúndún 5K Regbey, àwọn Byzantine ní ọ̀rúndún 6K, àti àwọn áráárábù ní Ọ̀rúndún 8..
wikipedia
yo
Lábẹ́ iledídúróayé Ottomani, Tunisia jẹ́ mímọ̀ bí “Ilu Nori/rẹkùn of Nori”
wikipedia
yo
Lẹ́yìn òmìnira ni 1956 orílẹ̀-èdè nã di “Ilẹ̀ọba Tùníṣíà” lẹ́yìn ìjọba Sulin Bey àti ìran-ọba husainid..
wikipedia
yo
pẹlu ifilọlẹ Orilẹ-ede olominira ará Tunisia ni July 25, 1957, Olórí ÀṣẹOlórílé-èdè Habib Bourguiba di Ààrẹ akọkọ.akiyesiitọkasi..
wikipedia
yo
Somalia tàbí Olómìnira Ilẹ̀ Somalia jẹ́ orílẹ̀-èdè ní ilaorun Afrika.Somalia jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Áfíríkà àríwá ila-oorun, níbi tí Òkun Pupa àti Òkun Indian jẹ́ èyà ti àwọn iṣowo ti Cen Sad, IGadgad, Afirika ilẹ̀ Áfíríkàjijù..
wikipedia
yo
NÀMÍBÍÀ tàbí orílẹ̀-èdè òtòayé ilé Namibia jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apágugúúsù Afrika.itọkasi..
wikipedia
yo
Olùjú (/plóyènwọn/ or US /p7VIpa:Jəə/ (from Carib via Spanish), papaw, (/pcasal: tabi PawPaw (/po:pọ̀,pọ̀: jẹ eso irugbincarica Papa, ti o si je mejilelogun awon ẹya idile carica ti ebi irugbin carica]].[Àwọn Ìtọ́kasí kukuru kukuru..
wikipedia
yo
Fred hampton (August 30, 1948 – December 4, 1969) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti igbákejì Alága ẹgbẹ́ olóṣèlú Black Panther Party ní Ìpínlẹ̀ Illinois.Ìtọ́kasí ọmọ Áfríkà Amél Kaage Adi ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Huey Percy Newton (February 17, 1942 – August 22, 1989) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Newton jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olórí ẹgbẹ́ òṣèlú Black Panther Party.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1942àwọn Ojoaláìsí ní 1989 Àwọn Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Black Panther Party (tí a mọ̀ sí Black Panther Party fún ìdáàbòbò fún Ara-ẹni ní ìgbà tí wọ́n kọ́kọ́ dá sílẹ̀) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú fún Ìdàgbàsókè àti ìpàdé àwọn aláwọ̀ dúdú ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lariǹ ọdún 1960 títí dé gbogbo ọdún 1970..
wikipedia
yo
Newton ati Bobby ṣeale ni wọ́n dá sílẹ̀ ní oṣù kẹwa ọdún 1966 ní Oakland ní Kaliakẹ́kọ̀ọ́yípadà.Àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú ní Us..
wikipedia
yo
Orilẹ-ede olominira arin Afrika jẹ orile-ede ni apa arin Afrika.itọkasi..
wikipedia
yo
{{Infobox Country|Nativenamename = Malawi (; Chichewa ), Loníbiṣẹ́ bi Orilẹ-ede Olómìnira Ilẹ̀ Màláwì, jẹ́ orílẹ̀-èdè Ademọarinlẹ̀ kan ní gúúsùilaọrun Afrika tó jẹ mí mọ́ tẹ́lẹ̀ bí ilẹ̀ Yejoté..
wikipedia
yo
Ó ní bodè mọ́ Zambia ní àríwáìwọ̀òrùn, Tanzania ní àríwáila, àti Mozambique ní ilaorun, gúúsù àti ìwọ̀òrùn..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè ná jẹ pínpínníyà sí Tanzania àti Mozambique pẹ̀lú omi-Adágún Màláwì..
wikipedia
yo
Màláwì tóbi tó pẹ̀lú àwọn alábùgbé ti ìdíye wọn ju 13,900,000 lọ..
wikipedia
yo
oluilu re ni Lilongwe, to tun je ilu tótóbijùlọ ni be; ikeji ni mejeeji ati orile ni Mzu..
wikipedia
yo
Màláwì bí orúkọ rẹ̀ wà láti Maravi, orúkọ àtijọ́ fún àwọn ńyanjà tí wọ́n bùdó sì bẹ́..
wikipedia
yo
Wọ́n tún unpé orílẹ̀-èdè yí bí “ọkàn alówóró Áfríkà".
wikipedia
yo
Buddhism (esin Budda)ibi Buddaìgbàgbọ́ ìbílẹ̀ fi hàn wí pé a bí Budda sí ìdílé ọba ní orílẹ̀-èdè "lumbini, Nepal ní àtẹ́lẹsẹ̀" lẹ́bá "Conyíndù..
wikipedia
yo
Nítorí náà, àwọn awòràwọ̀ wí pé ní ìlú “Kalra” èyí tí ó ti di òrìṣà àkúnlẹ̀bọ ní ìlú “India” ni a gbé bí i..
wikipedia
yo
Kò sí ẹni tí ó mọ Àkọsílẹ̀ ọjọ́ ìbí rẹ̀ pàtó tàbí tí ó ní àkọsílẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Olukuluku kan nsọ awọn ojo ti wọn ro pe o le jẹ ni nitori ko si àkọsílẹ̀ kan pato ti a le tọka si..
wikipedia
yo
Àwọn òǹìtàn kan ni a bí i ní ọdún “623 tàbí 624 BC”
wikipedia
yo
Kò pẹ́ kò jíiná yìí ni àwọn ẹlẹ́sìn kan sọ wí pé ọjọ́ ìbíi rẹ̀ títí di ọjọ́ tí ó gbé lórí èèpẹ̀ jẹ́ ní àárín ọdún 567 sí 487 BC" .Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n wí pé a bí i ní ọdún 420 sí 502 BC" kí a má fi ọ̀pá Polopọlọ pa ejò, kò sí ìdánilójú ọjọ́ ìbíi rẹ̀ àti ọjọ́ tí ó lò láyé..
wikipedia
yo
Àwọn ohun tí a rí ninu àkọsílẹ̀ tí ó ṣe pataki ni pé a bí i ní ọ̀nà ìyanu..
wikipedia
yo
Léhìn ìbí rẹ̀, ó dìde dúró ó gbé àwọn ìgbésẹ̀ nínú èyí tí ó kéde ara rẹ̀ wí pé òun yóò jẹ́ ìjòyè ayé..
wikipedia
yo
Ó wí pé èyí ni yóò jẹ́ ìgbà tí òun yóò padà wá sáyé gbẹ̀hìn..
wikipedia
yo
Orúkọ tí àwọn òbí rẹ̀ sọ ọ́ ni “Àmìra Gautama”
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí “ẹni tí ó ti kẹ́sẹ járí ṣùgbọ́n ”Gautama” ní orúkọ ìdílé tí a bí i sí..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ ìgbà ni wọ́n ma ń pè é ní “Númérì] ìtumọ̀ èyí tí ń jẹ́ amòye ninu “Baaliyas”
wikipedia
yo
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ "SAK" jẹ́ ẹni tí a tọ́ lọ́nà ẹ̀sìn "Hindu", ero àwọn òbí rẹ̀ ni kí ó jẹ́ àarọ́pò bàbá rẹ̀ lẹ́hìn ìgbà tí ó bá gbé́n láá́n..
wikipedia
yo
Wọ́n rò wí pé yóò láǹfààní láti jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká ọba tàbí olórí ẹ̀sìn nlá kan tí ó ṣe jìnmọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ toô ní ọ̀nà ọlá àti ọlà kí ohun tí ó wá ṣe l'ayé lè rọrùn fún-un àti kí ó lè gbé ìgbé ayé ẹ̀sìn wọn..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ni ó gbé ìyàwó, orúkọ ìyàwó rẹ̀ a má jẹ́ “SodHara", nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mọkandinlọgbọn ni ìyàwó rẹ̀ bí ọmọ ọkùnrin kan fún-un orúkọ rẹ̀ a má jẹ́ "Wmọ́tò"
wikipedia
yo
Lẹ́hìn tí ó bí ọmọ yìí tán ìtàn fi yé wa wí pé ó ṣe ìrìnàjò lórí ẹ̀sìn lẹ́ẹ̀mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, nígbà tí ọ̀pọ̀ ìtàn sọ wí pé ń ṣe ni ó rí ìran lẹ́ẹ̀mẹ́rin..
wikipedia
yo
Nínú ìrìnàjò rẹ̀ àkọ́kọ́ ó rí ọkùnrin arúgbó kan tí ó jẹ́ aláìlólùrànlọ́wọ́, ní ìrìnàjò rẹ̀ kejì ó rí ọkùnrin tí àìsàn tí ó lágbára jùú ló ń bá a fínra, ní ìrìn àjò rẹ̀ kẹta ó rí ìdílé kan tí ìbànújẹ́ bò mọ́lẹ̀ tí wọ́n sì ngbé ọ̀kan nínú wọn tí ó ṣe aláìsí lọ sí ibojì..
wikipedia
yo
Ó ronú jinlẹ̀ lórí ìṣòro tí àwọn arúgbó ń kojú bí àìsàn àti ikú..
wikipedia
yo
Nínú ìrìn àjò rẹ̀ kerin, ó rí ẹlẹ́sìn kan tí ó pé sí ìrònú nípa ohun tí ó rí nígbà yìí ni ọkàn rẹ̀ tó ru sókè láti tẹ̀lé ọ̀nà àti lè ṣe ìrànlọ́wọ́ nípa ti ẹ̀mí pãpã fún ìṣòro tí ó ń kojú ọmọ ènìyàn.Ó fi aya, ọmọ àti ìgbé ayé ìrọ̀rùn àti ìgbà ayé aṣáájú àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀ láti ṣe ìwãdí ìyànjú ìsọ̀rọ̀ ẹ̀dá.Ní àkókò náà àwọn ọkùnrin míràn a má kúrò ní ilẹ̀ láti lọ d'anìkàn wà nínú igbó tàbí ibití ó ṣe kọ́lọ́fín nítorí wọ́n fẹ́ mọ àwọn ohun ìjìnlẹ̀ kan..
wikipedia
yo
Wíwá ọ̀nà sí ìṣòro tí ó ń ko ẹ̀dá lójú ó kọ́kọ́ gbìyànjú láti ronú ohun tí ó kọ láti ọ̀dọ̀ àwọn olùkọ́ rẹ̀ méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, ó rò wí pé èyí ni ó ṣe iyebíye.Ṣùgbọ́n ìrònú yìí kò lè tẹ̀síwájú lọ títí nítorí náà ó yípadà nínú ìrònú náà kí ó lè dojú kọ àwọn ìṣòro náà tí ó ń fẹ́ yanjú èyí, tí ó jẹmọ́ ìbímọ, àìsàn ọjọ́ ogbó àti ikú..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tí wọ́n jọ ní èrò kan lórí wíwá ọ̀nà sí ìṣòro tí ó ń dojúkọ ènìyàn, ní bẹ́ẹ̀ ni ó ti kó onírurú ohun bí kí a ṣe èémí àti bí a ti gba àwẹ̀ léraléra..
wikipedia
yo
Àwọn ohun tí o gbékalẹ̀ fún ara rẹ yìí jẹ ohun tí ó nira lọpọlọpọ nítorí náà ó fi sílẹ̀ láì tún tẹ̀síwájú nípa rẹ mọ́, àwọn tí o ṣe fífi ìyà jẹ ara ẹni gbga àwé tàbí sìn rẹ “Hen” kò sí ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro tí ó nfẹ́ ìyànjú nítorí náà ó tún pinnu láti ṣe àwárí ọ̀nà míràn láti lè tú àwọn ènìyàn sílẹ̀ nínú ìṣòro tí ó ń dojú kọ wọ́n..
wikipedia
yo
Àwọn ìfòye dddani aṣálẹ̀ ọjọ́ kan ni “535 BC” ní ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún márùndínlógójì ó jòkó lábẹ́ igi ńlá kan tí a mọ̀ sí igi bòdí..
wikipedia
yo
(1)Ní alẹ́ àkọ́kọ́ ó rántí ìgbé ayé kí a kú ní ibìkan kí a sì tún wà ní ibòmíràn gẹ́gẹ́ bí alààyè..
wikipedia
yo
(2)Ní alẹ́ òjì kejì ó rí bí ìgbé ayé ibi àti ìkà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ má ń gbé ṣe ma ń sọ ibití wọn yóò lọ lẹ́hìn ikú.(3)Ní alẹ́ ọjọ́ kẹta ó kọ́ wí pé òun ti tẹ̀síwájú kọjá ipele bíba èmi jẹ́ nípa ikorira, ìbínú, òǹgbẹ, ìbẹ̀rù àti ìjayà ó sì pinnu wí pé òun kò tún ní wá s'ayé mọ́..
wikipedia
yo
O ti ní fifihàn ọ́ sì di “Olùgbàlà, ẹnitó ń gbani àti Olùràpadà” lẹ́hìn ìfòye rẹ yí ọ gbiyànjú lati jẹ kí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ nípa pípolongo ẹ̀kọ́ rẹ si wọn èyí ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ si gbàgbọ́ ti wọn sì ń tẹ̀lé ẹ̀kọ́ rẹ...
wikipedia
yo
Ìmọ̀-ìṣègùn jẹ́ ìmọ̀ tàbí ìwádìí ohun tí ó ń fa àìsàn, àti ọ̀nà tí a lè gbà ṣe ìtọ́jú irúfẹ́ àìsàn tàbí kí a ṣe àmójútó rẹ̀, tàbí kí a pèé ní ìmọ̀ ti fi ń dá àìsàn lọ́wọ́ kò àti àwọn oríṣiríṣi ìpalára tí ó lè fà sínú àgọ́ ara ..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ ìṣègùn jẹ́ ìmọ̀ àti ọ̀nà ọgbọ́n nípa ṣíṣe ìtọ́jú àti ìmú padà-sípò tàbí ìràpadà àlàáfíà fún ènìyàn nípa àṣàrò, ìwádìí ohun tí ń mú àìsàn wá àti ìtọ́jú fún àwọn aláìsàn..
wikipedia
yo
Iṣẹ imọ iṣẹgun ti igba ìsisìyí han pupọ, bi ẹkọ iwosan ati gbogbo iwadii imọ iṣẹgun fun awon aisan ti wọn sese jade..
wikipedia
yo